cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Bàbá Mandela fẹ́ iyàwó mẹ́rin, ó sì bi ọmọ mẹtala (13) ọkùnrin mẹ́rin àti obìnrin mẹsan-an..
wikipedia
yo
Fanny jẹ́ ọmọbìnrin nkédama lati iran mpemvu Xhosa, ọ̀tún Ọba, ninu ilé ẹni ti Mandela ti lọ ìgbà ọmọdé rẹ̀..
wikipedia
yo
Orúkọ àbísọ rẹ̀ Àlìkámà túmọ̀ sí "Fá ẹ̀ka igi", "Reoníjàngbọ̀n". Mandela lo je ọmọ àkọ́kọ́ nínú ẹbí ẹbí rẹ̀ tó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ti olùkọ́ rẹ Miss MGANganẹ ti fún un lórúkọ Geesi "Nelson".Nigba ti Mandela to ọmọ ọdún mẹsan-an, bàbá rẹ ku nipa iko ẹgbẹ (BBB), nitori eyi Jongin, di alagbaalágbàtọ́ rẹ..
wikipedia
yo
Mandela lọ si ilé ẹ̀kọ́ ti ó jìnnà si ààfin jokogintábà..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú bí àṣà thembu ṣe là á sílẹ̀, ó jẹ́ sísọ dàgbà nígbà tó tó ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16), ó sì relé ẹ̀kọ Clarkebury boarding Institute..
wikipedia
yo
Mandela pari ilé ẹ̀kọ́ ọ̀dọ́ láàarín ọdún meji, kàkà ọdún mẹta tó yẹ..
wikipedia
yo
Lèyí to jẹ yiyan lati jogún ipo baba rẹ gẹ́gẹ́ bi alámọ̀ràn ọba, ní ọdún 1937 Mandela kò lọ sí HAMRetown Comprehensive School, kọlẹji àwọn ẹlẹ́ṣin Wesley ní Fort Beaufort ti ọ̀pọ̀ àwọn àwọn ọmọ olóyè ní thembu tí n lọ sí ilé-ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọmọ ọdún mọ́kàn-dínlógún (19) ó fẹ́ràn lati já ẹsẹ̀ àti erésísá ní ilé-ẹ̀kọ́.Lẹ́yìn tó tó dé kọ́lẹ́jì, Mandela bẹ̀rẹ̀ sí keko fún iwé-ẹ̀ri Bachelor Iṣẹ-ọna ni Fort hare University, níbi tó ti pàdé Oliver Tambo..
wikipedia
yo
Mandela tun di ọrẹ pẹlu rúwé ("K.D.”) Matanzima eni to je gege bi Oloye ọ̀túnba thembu wa lori ila fun ite ni transkéKe, eyi ti yio fa lọjọ iwaju lati tẹ́wọ́gba eto Bantuus..
wikipedia
yo
Ìtìlẹ́yìn rẹ fún àwọn ẹ̀tọ́ yí fa ìlòdì lãrín ọ̀hún àti Mandela..
wikipedia
yo
Ni ẹ̀yin ọdún mue ni kọlẹji Mandela kópa ninu boikotu ti Igbimọ Awọn Aṣoju akeko ṣe nitori àwọn ètò Yunifasiti, nitoriẹ wọn le kuro nibe..
wikipedia
yo
lọjọ nígbà tó wà ní ọgbà ẹ̀wọ̀n, Mandela kẹkọ fún iwe-ẹri Bachelor Ofin lati ibi eto Okere Yunifásítì Lọndọnu.Rereré tó kúrò ní Fort hare, Jongtaba sọ fún Mandela àti Justice (tó jẹ́ ọmọ Jóginta àti ẹni tó kan láti jọba) pe ohun tí ṣètò ìgbéyàwó fún àwọn méjèèjì..
wikipedia
yo
ṣùgbọ́ àwọn méjèèjì nítorípé wọn kò fẹ́ràn ètò ìgbéyàwó yí, wọ́n kọra wọ́n sì kọ lọ sí Johannesburg..
wikipedia
yo
Nígbà tó dé bẹ̀, Mandela níbẹ̀rẹ̀ kọ́kọ́ rí iṣẹ́ bi aṣọ́nà ninu kòtò àlùmọ́nì..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n, ẹni tó gbà ṣíṣẹ́ tètè yára le kúrò nígbà tó gbọ́ pé Mandela jẹ́ alágbàtọ́ ọba..
wikipedia
yo
Mandela lẹ́yìn na bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ bi akọ̀wé ni ilé-iṣẹ́ àgbẹ̀jọ́rò tó wà ni Johannesburg, Witkin, Sidels àti Edelman, láti ọ̀dọ̀ ọ̀rẹ́ àti aláwòṣe rẹ̀, Walter Ṣíṣu..
wikipedia
yo
bó ṣe únṣiṣẹ́ ní ìlúgkin, Sidels àti Edelman, Mandela parí iwe-ẹri B.A..
wikipedia
yo
Oun ni Yunifasiti guusu Afrika pelu Ìfiranṣẹ, leyin na lo wa bere si ni Deti ofin ni Yunifasiti Witwatersrand, nibi to ti bere si ni soro awon elegbe akoko re ati awon alákitiyan àpàr orirthe lọjọwaju Slovo tàbí Harry ati Ruth first..
wikipedia
yo
Slovo yio wa di alakoso ọrọ ile ninu ijoba Mandela lọjọwaju, nigbati Schwarz yio di aluṣoju guusu Afrika ni Amerika..
wikipedia
yo
Ní àsìkò yìí, Mandela gbé ni Alexandra, tó wà ní àríwá Johannesburg.Ìgbésẹ̀ òṣèlú lẹ́yìn tí ẹgbẹ́ òṣèlú ẹgbẹ́ ọmọorílẹ̀-èdè ẹgbẹ́ òṣèlúAFÉ nínú ètò ìdìbò ọdún 1948, nítorípé àwọn wọ̀nyí fọwọ́ mọ́ ètò àparthed's àpàrthed' àpar àpà's ẹlẹ́yà-mẹ̀yà, Mandela bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa gidigidi nínú ọ̀rọ̀ òṣèlú..
wikipedia
yo
Ó síwájú nínu kampe agídí tí anc ṣe ní 1952 àti nínú Kongṣi àwọn ènìyàn ní 1955 ti pinu tí àbájáde rẹ̀ jẹ́ ìpìlẹ̀ ètò ìlòdì sí iṣẹ́ ẹlẹ́yà-mẹ̀yà àpar àpàd..
wikipedia
yo
Leti àsikò yi, Mandela àti orisun rẹ Oliver tambọ̀ dá ilé-iṣẹ́ agbẹjọ́rò man'del àti tambọ̀ silẹ lati pèsè ìmọ̀ràn òfin ọ̀fẹ́ fún ọ̀pọ̀ àwọn Aláwọ̀dúdú ti wọn kò ni Agbẹjọro.Ma6 Gandhi nipa ìhà ti Mandela àti bi àwọn ọ̀nà ti àwọn alákitiyan olódi àpàrTheid gúúsù Áfríkà fi kojú rẹ..
wikipedia
yo
Titan MvuyeFÚN Mbeki tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù Kẹfà Ọdún 1942 (18 June, 1942) jẹ́ Ààrẹ àna orílẹ̀-èdè gúùsù Áfíríkà láti ọdún 1999 títí dé 2008.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn Ààrẹ ilẹ̀ Gúúsù Áfríkà..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Ilẹ̀ Gúúsù Áfíríkà wà ní ẹnu igun apá gúúsù Áfíríkà..
wikipedia
yo
Brasil (, ), Loníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Bani Ilẹ̀ Brasil (fèdè Republic of Brazil (, ), ní Orílẹ̀-Èdè tótóbitó ní Guusi Amẹ́ríkà àti ní agbègbè Amẹ́ríkà Látìnì..
wikipedia
yo
Okòwò rẹ̀ ni ikaarun tótóbito lágbà, gegebi ala Jeografi ati bii alabùgbé pẹlu 193 million eniyan..
wikipedia
yo
Brasil ni orile-ede eledeṣọ́ tótóbitó lagbaye, ati ikan ṣoṣo ni orile awon Amerika.O ni Bode mo Okun Atlantiki ni ilaọrun, Brasil ni Etiomi to to ..
wikipedia
yo
O ni bodè ní àríwá pẹ̀lú Venezuela, Guyana, Suriname àti agbègbè ọ̀kẹ́rẹ́ Fránsì ní Guiana Fránsì; ní àríwáìwọ̀ pẹ̀lú Kolopajú; ní ìwọ̀òrùn pẹ̀lú Bolivia àti Peru; ní gúúsùìwọ̀ pẹ̀lú Argentina àti Paraguay àti ní gúúsù pẹ̀lú Uruguay..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àwọn Erékùṣù Oṣùpọ̀ wà ní ará ilé Brasil, bí Fernando De Noronha, Rocas ALL, Saint Peter and Paul Rocks, àti Trindádé and MarTim Vaz..
wikipedia
yo
O ni Bode Mo gbogbo awon orile-ede guusu Amerika àyàfi EkuṢilo ati Tsile.Brasil tele je imusin Portugal latigba ti Pedro AlCHA Carobral gunle sibe ni 1500 titi di 1815, nigba to di Ilẹ̀ọba ati Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Portugal, Brasil ati awon Algafe je dídásile..
wikipedia
yo
ìbáṣe àmúsìn na jẹ gígé ni 1808, nigbati oluilu ileỌbalúayé Alamusin Portugal jẹ gbigbe kuro ni Lisbon lo si Rio de Janeiro, leyin igba ti Napoleon gbógunlu Portugal..
wikipedia
yo
Brasil gba OlaLásárù ní 1822 pẹ̀lú ìdásílẹ̀ ileỌbalúaye ilé Brasil, orílẹ̀-èdè Asọṣọ̀kan pẹ̀lú Irú Ìjọba Kábíyèsí Oninlácanpo ati Sistemu Apan..
wikipedia
yo
Brasil Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Oniare ni 1889, nígbà tí ìfipágbàjọba ológun Sakede Orílẹ̀-èdè Olómìnira, Bótilẹ̀jẹ́pé Iléaṣòfin oníyẹ̀wù méjì, lọni tó ń jẹ́ Kongrésì, ti wá láti ìgbà Ìtọwọ́bọ̀wé ìldi Àkókò ní 1824..
wikipedia
yo
ìlànupo Brasil loni, tó jẹ́ dídá ní 1988, pé Brasil ni Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀..
wikipedia
yo
Ìparapọ̀ Orílẹ̀-èdè ná wáyé pẹ̀lú ìṣọ̀kan lãrín agbègbè ìjọba àpapọ̀, àwọn ìpínlẹ̀ 26, àti àwọn agbègbè ìbílẹ̀ 5,564.Okòwò Brasil ni ìkẹfà tótóbijùlọ lagbaye Gẹ́gẹ́bí GD Olórúkọ àti Ìkeje tótóbitó gẹ́gẹ́bí òṣùwọ̀n agbára Ìnáwó (titi dé 2011)..
wikipedia
yo
Brazil ni ikan ninú àwọn okòwò gbàngbà tó únsáré dàgbà jùlọ lágbáyé..
wikipedia
yo
Àwọn àtúnṣe okòwò tó wáyé ti fún ní ìdámọ̀ tuntun káríayé..
wikipedia
yo
Brasil jẹ́ ọmọẹgbẹ́ olùdásílẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè Aṣọ̀kan, G20, CP, isokan Latini, Àgbájọ àwọn orílẹ̀-èdè Iberia Amẹ́ríkà, Àgbájọ àwọn orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, Mercodd àti isokan àwọn orílẹ̀-èdè Gúúsù Amẹ́ríkà, àti ìkan nínú àwọn orílẹ̀-èdè Bric..
wikipedia
yo
Bákana Brasil tún jẹ́ ìkan nínú àwọn àwọn orílẹ̀-èdè olóhùn-oríṣiríṣi 17, ibẹ̀ jẹ́ ilẹ̀ fún àwọn oríṣi ẹran ìgbẹ́, àyíká àdánidá, ọ̀pọ̀ àwọn àlùmọ́nì àdánidá níbi oríṣi ibi abo..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà 67 àbínibí tí wọ́n dá dúró, Brasil ni iye àwọn ènìyàn aìtípàdé tó pọ̀jùlọ lágbà.Ìtumọ̀ orúkọọ̀ruko rẹ̀ bí "Brasil" wá lati oruko igi Brasil, igi kan tó ń wù nígbàkan ni nuit rere leti Ẹ̀bá Ẹ̀ta Brasil..
wikipedia
yo
Ní èdè Portugal, igi Brasil únjẹ Pau-Brasil, níbi tí Brasil ti túmọ̀ sí "pupa bí ojúina", láti èdè Latin Brasa ("ember") àti Alemẹ̀yìn -il (lati -ICulum tàbí -Ilium)..
wikipedia
yo
Nítorípé igi Brasil ṣe dá aró pupa, ó níyì yínyín ní Europe láti fi kún aṣọ, ohun sì ni ajẹ́ àkọ́kọ́ tó wúlò lati Brasil..
wikipedia
yo
kákiri ìgbà ọ̀rúndún 16K, ọ̀pọ̀ igi Brasil jẹ́ fífí látọwọ́ àwọn ènìyà àbínibí (àgàgà àwọn Tupi) lẹ́ba Etiomi Brasil, àwọn yí sí tà wọ́n fún àwọn oníbùkátà ará Europe (àgàgà àwọn ara Portugal, àti fún àwọn ará Fránsì) fún pàṣípàrọ̀ fún oríṣi Ọjà àmúlò láti Europe..
wikipedia
yo
Oruko oníbiṣẹ́ ile yi, ninu awon akosile awon ara Portugal, je was the "ile agbelebu mimọ" ("land of the Holy Cross”; Terra da Santa Cruz), sugbon awon awako-ojúomi ati ọlọ́jà ará Europe unsaba pe lasan bi "Ile Brasil" ("land of Brazil”; Terra do Brasil) nitori bùkátà igi Brasil..
wikipedia
yo
Orúkọ yí ló gbajúmọ̀ títí dọ̀ ní tó fi rọ́pò orúkọ oníbiṣẹ́..
wikipedia
yo
Bakanna awon awako ojúomi níbẹ̀rẹ̀ pe ibe ni "Ile awon Oroko" ("land of Parmejì”; Terra di papaga).Ní ede guArani, ti se ede oníbiṣẹ́ kan ni Paraguay, Brasil únjẹ pipe ni "Wagaka"
wikipedia
yo
Oruko yi ni awon eniyan abinibi fun agbegbe yi, itumo re ni "Ile awon igi ope" ("land of the palm trees"). biàmúsìn Portu ile ti a mo loni bi Brasil je gbigbesele latọwọ Portugal ni April 1500, nigba ti oko-ojúomi lati Portugal ti Pedro Altical cabral dari gunle..
wikipedia
yo
Àwọn wọ̀nyí pàdé àwọn aré ibẹ̀ tí èdè opó wọn jẹ́ ti túpí-guùn..
wikipedia
yo
Bótilẹ̀jẹ́pé ìlú Abudo àkọ́kọ́ jẹ́ didasilẹ̀ ní 1532, imusin kọ́ bẹ̀rẹ̀ títí tó fi di 1534, nígbàtí ọba dom João 3 Ilé Portugal Portugal ibẹ̀ ibẹ̀ sí ilé Baṣọ̀run ará méjìlá..
wikipedia
yo
Eto yi ko ni yori i rere rara, bọ́sí ti di ọdún 1549 Ọba yan Gómìnà àgbà kan láti samójútó gbogbo ibẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà abinibi bí melo kan jẹ́ fíyìmọ́, àwọn míràn jẹ́ kíkó̀rù tàbí píparun nínú ogún tàbí pẹ̀lú àwọn àrùn tí àwọn ará Europe kò ran wọ́n tí ara wọn kò ní Àjẹsára sí..
wikipedia
yo
Nígbà tí yíò fi di àrin ọ̀rúndún 16K, suga ti di ọjà òkèrè pàtàkì fún Brasil nítorí àwọn ara Portugal yí kọ́ ọ̀pọ̀ ẹrù wa láti Áfríkà láti fi wọ́n ṣiṣẹ́ fún ìbẹ̀rẹ̀ ọjà ṣúgà tó únpọ̀ sí káríayé.Nípa gbígbógun ti àwọn ará Fránsì, àwọn ara Portugal díẹ̀díẹ̀ fẹ́ ilé wọn dé gúúsùilaòrùn, wọ́n sì gbẹṣẹ̀lẹ̀ ìlú Rio de Janeiro ní Bánà, àti dé àríwáìwọ̀òrùn, níbi tí wọ́n ti gbẹ́ṣẹ̀lẹ̀ ìlú São Luis ní 1615..
wikipedia
yo
Wọ́n rán àwọn ológun lósì igbó-aginjù Amasọni wọ́n sì borí àwọn ajagun Britani àti Horlán tọ̀ wá níbẹ̀, kí wọ́n ó tó bẹ̀rẹ̀ síní dá abúlé àti ilẹ̀ ológun síbẹ̀ láti 1669..
wikipedia
yo
Ní 1680 wọ́n dé gúúsù níbi tí wọ́n da Sacramento sílẹ̀ sí ní ẹ̀bá Rio de la plata, ní agbègbè Etiomi Apáilaọrun region..
wikipedia
yo
Ni opin orundun 17K, oja suga ni Okere bẹ̀rẹ̀ sí ní re sílẹ̀ ṣùgbọ́n láti ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 1690, àriri Wúrà Látọwọ́ àwọn Olùwákiri ní agbègbè na tó dára pípẹ́ ní Minas Gerais ní Mato Grosso àti Goiânia loni, gba ibi àmúsìn na là lá iparun..
wikipedia
yo
kákiri láti Brasil, àti láti Portugal, ẹgbẹẹgbẹ̀rún ènìyàn tú wa sí kòtò àlùmọ́nì láti wá ṣiṣẹ́..
wikipedia
yo
Awọn ara Spepe gbira lati dena awọn ara Portugal lati fe ile won de ori ile to je ti won gegebi adehun Torllasllas 1494, won si yori lati gbesele Etiomi apailaọrun ni 1777..
wikipedia
yo
Sibẹsibẹ, asan ni eyi jasi gegebi adehun San Ildetso, ti won fọwọsi lodun kanna yi, sedaju ase Portugal lori gbogbo awon ile ti won ba gbesele, ati igba yi ni opo gbogbo bodè Brasil loni ti wa..
wikipedia
yo
Ni 1808, ebi ile-ọba Portugal ati opo awon ijoye Portugal, lati BO lowo awon ajagun Napoleon I lati Fránsì ti won ungbógun ti Portugal ati gbogbo arin Gbọ̀ngàn Europe, ko ara won lo si ilu Rio de Janeiro, to fi be di ibujoko gbogbo ilelululu Portugal..
wikipedia
yo
Ni 1815 dom João 6K, gege bi áruobá Dipo iya re, gbe Brasil soke lati ibi àmúsìn di alase Kingdom United with Portugal|Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan ile Portugal, Brasil ati awon Algarfe..
wikipedia
yo
Ni 1809 àwon ara Portugal na tun gbógun ti Guiana Fránsì (ti wọ́n dá padà fún Fránsì ní 1817) bẹ sini ní 1816 wọn yí ọ̀runkọ Etiomi Apailaọrun sí cispLatina.Olatàbi ati Ilẹ̀obáografi ati Ìṣèlú Ìpínlẹ̀awọn Ìpínlẹ̀ ati Ibileará Ìtọ́kasí Awọn Orilẹ-ede Ijọba-ede Aapapọ̀ Ile àmúsìn Portugal tẹlẹ Àwọn Orilẹ-ede KaGiye Ala-ede Guusu AlaAmégbọ̀n Kaf Ouse Okunlẹ-ede Elebo ElePotogí A-ede to ni Bode Mo Okun Odu Atlantiki..
wikipedia
yo
Òkun jẹ́ gbogbo omi oníyọ̀, àti èyí tó ṣe pàtàkì ará ilẹ̀-ayé..
wikipedia
yo
Òjò jẹ́ omi tí ó ń ro láti sánmọ̀, tí ó sì ń di omi ní orí ilẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àǹfààní ni omi tí ó ń sọ̀kalẹ̀ yí ń ṣe fún ọmọ ènìyàn, lára rẹ̀ ni a ti ń pèsè iná mọ̀nàmọ́má, ó wúlò nínú ilé, ó wúlò fún mímu, ìdáná àti ìtọ́jú oúnjẹ, ó wúlò fún ìwé, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Síwájú sí, omi ojo tún wúlò fún ìdàgbàsókè àwọn nkan ọ̀gbìn wa gbogbo.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Fela Anikulapo Kuti (oruko ibi Olufe Olusegun Oludotun Ransome-Kuti, October 15, 1938 – August 2, 1997) tabi Fela je olorin omo orile-ede Naijiria, o tun je adija-gbara fun awon omo orile-ede edeNaijiria; o si tun ma n ko orin..
wikipedia
yo
wọ́n mọ̀ọ́ sí ẹni tí ó o síwájú orin àwọn aláwọ̀ dúdú..
wikipedia
yo
Oruko miiran ti won a maa pe Fela ni "Abàmì Ẹ̀dá."Fela Kuti je omo Adija-gbara fun eto awon obinrin, iya ààfin Funmilayo Ransome Kuti..
wikipedia
yo
Ni igba ti o de lati ilu Oyinbo, orin rẹ kan ti o n jẹ "Africa '70" jade ni ọdun 1970..
wikipedia
yo
Ní ọdún yí i ni ó fi orin rẹ̀ bá àwọn ìjọba alágbádá tó wà ní'pọ̀ wí i.[3] Ní ọdún yìí náà ni ó dá “Kalakuta Republic commún” si'lẹ̀, tí ó sì yọ ara àlà rẹ̀ kúrò láàrín in àwọn tó ní’fẹ́ẹ́ sí ìjọba alágbádá..
wikipedia
yo
Ìjọ “Comrio” yìí padà dàrú ní ọdún un 1977 ni'gba tí wọ́n dá’na sun-ún..
wikipedia
yo
Láti ìgbà tí Fela Kuti ti di olóògbé ní ọmọ rẹ̀, Femi Kuti, ti kó gbogbo orin rẹ̀ jọ s'ojú kan.ìbẹ̀rẹ̀ ayé e rẹ̀bíolu Olusegun Oludotun Ransome-Kuti ni wọ́n bí ní ọdún un 1938, ní ọjọ́ karùndínlógún osu ọ̀wàrà (October 15) sí ìlú U Abeokuta, ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bi a ṣe mọ̀ pe adija-gbara fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin ní ìyá a rẹ̀, Oloye Funmilayo Ransome-Kuti, tí bàbá rẹ̀ sì jẹ́ olùṣọ́ àgùntàn ti ijọ Anglican, olukọ-agba ati Ààrẹ fún gbogbo olùkọ́..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ ìyá rẹ̀ ni bẹ́ẹ̀kọ́ Ransome-I àti Olìkọọ̀gá Ransome-Kuti, Dókítà ìlúmọ̀ọ́ká Dókítà..
wikipedia
yo
Fela tun tan mo ojogbon wole Soyinka, eni ti o je eni akoko ni ile alawo dudu ti o gba ebun iyi Litireso (Nobel Prize in Literature).Kuti lo si ile iwe girama ti ilu u Abeokuta..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1958, o lọ si oke okun lo ka ẹkọ imọ iṣẹgun..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n, ó padà lọ sí ilé ìwé ẹ̀kọ́ orin kan tí wọn ń pè ní Trinity College of music..
wikipedia
yo
Ní’gba tí ó wà l’ohùn un, ó dá ẹgbẹ́ orin ti tirẹ̀ sí'lẹ̀, tí ó ń jẹ́ "Kkoola Lobis", tí wọ́n ń kọ "Jazz" àti “Highlife..
wikipedia
yo
Ni odun 1960, Fela fe iyawo o re ti oruko re n je pààlà Kuti, eni ti o si bi omo meta fun; oruko won a si ma a je Femi, Yemi ati Sola..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1963, kútí padà sí Nàìjíríà l'ẹ́yìn ìgbà tí ó ti gba òmìnira; ó sì ń kó ẹgbẹ́ orin rẹ̀ káàkiri..
wikipedia
yo
ní ọdún 1967, Kútì lọ sí orílẹ̀ èdè Ghana láti lọ wá ọ̀nà mìíràn bí yo ó ti ma a pe orin rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀nà ìpè orin mìíràn tí ẹ yí i wà ní “afrobeat”, ìyẹn tí ń ṣe àpapọ̀ “Highlife”, ”fún “Jazz", “Sal”, “calypso” àti orin ìjìnlẹ̀ ilẹ̀ Yorùbá.Bí Fela ṣe jà fún ètò ará ìlù bí Fela ti ṣe ń ṣe ìjà-n-gbara, bẹ́ẹ̀ni wọ́n ń fi pamọ́ sí àgọ́ ọlọ́pàá..
wikipedia
yo
Ní gbogbo ìgbà tí ó bá fi ẹ̀hónú hàn ni wọ́n máa mú lọ sí àtìmọ́lé, bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n á má a fi ìyà jẹ àwọn ìyàwó àti àwọn ọmọ rẹ̀.Fela Kuti jẹ adijà-gbara fún ẹ̀tọ́ o ará ìlú tí tí ó fi di olóògbé..
wikipedia
yo
Kuti a maa dojú kọ ijoba Naijiria fun gbogbo iwa ibaje ti wọn wu si àwọn ará ilú ti wọn fi wọn si ipò..
wikipedia
yo
Fẹlá jẹ́ ki wọn mọ pé àwọn òyìnbó ni wọ́n dá rògbòdiyàn si ilu Naijiria..
wikipedia
yo
Ayẹyẹ ọdọọdun kan si wa, ti wọn n pe ni "Felabration lati fi maa se iranti olóògbé Fela Kuti gẹ́gẹ́ bí i eni orin rẹ̀ wuyì l'áwùjọ..
wikipedia
yo
ní ọdún 1999, Universal Music France, ní abẹ́ ẹ̀ ìdarí i Francis Kertekian, gbé àábọ́ọ̀mù ogóòjeji ó lé márùn ún (àrùn-din-laadota) ti Fela jade..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ sì tún ni Fela tún gba oríyìn àti àmì ìpègede l'ókè òkun.Olórin kan tí wọ́n ń pè ní Ṣól láti orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tún orin Fela se ní ọdún 1997 tí ó sì pe àkọ́lé ẹ̀ rẹ̀ ní "Sorrow, Tears and Blood"
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007 ni eré orí ìtàgé kan tí àkọọ́lẹ̀ rẹ̀ ń jẹ́ "The Visitor" (àlejò) tí arákùnrin kan tó ń jẹ́ Thomas McCarthy darí jáde..
wikipedia
yo
Eré yí i ṣe àfihàn an ọ̀jọ̀gbọ́n kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Richard jẹ́kins, ẹni tí ó fẹ́ gbọ́ orin kan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ “djembe” tí ó kọ láti ọ̀dọ̀ arákùnrin kan tí à ń pè ní Háàz Sleiman ẹni tí ó wá láti orílẹ̀-èdè Syria..
wikipedia
yo
Háàz Sle: sì sọ fún ọ̀jọ̀gbọ́n yìí pé kò sí bí òun ṣe lè gbọ́ àgbọ́yé orin àwọn aláwọ̀ dúdú àyàfi tí òun bá kọ́kọ́ gbọ́ orin Fela..
wikipedia
yo
Nínú eré yìí náà ni wón ti ṣe àfíhàn orin Fela méjì kan ti àkọ́lé e wón n je "Open and close" àti "jệ n wi temi"
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n fún ní orísirísi ẹ̀bùn tó pọ̀ já-n-ti-rere..
wikipedia
yo
Wọ́n sì tún fa a ka'lé ní èmọ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i ẹni tó yẹ láti gba ẹbùn ìpéré Títayọ nínú iṣẹ́ orin kiko.Awon aṣayan orin tí ó kọ sílẹ̀ "Fela Fela Fela Fela ní ọdún 1969, live! (1971rokunnunu jade ní ọdún 1972"SHkara" ní ọdún 1973"Open & Close" ní ọdún 1971 "AFelàkókòc" jade ní ọdún 1973"Wo jade ní ọdún 1973"ConConCon[Con) jade ní ọdún 1975"Expensive Shit" jade ní ọdún 1975"he Miss Road" jade ní ọdún 1975"water no get enemy" jade ní ọdún 1975.J..D..
wikipedia
yo
Desmond Suïlo Tutu (Ọjọ́ Ìbí 7 October 1931 - 26 December 2021) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Gúúsù ÁfríkàÌtọ́kasí Ọjọ́ìbí ní 1931Àwọn ẹlẹ́bùn Nobel fún Aládunni ẹlẹ́bùn Nobel ará gúúsù Áfríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọdún 1895 Látọwọ́ ará Sweden Onímọ̀ ẹ̀kọ́ Élà (Kemistri) Alfred Nobel, olùṣe Ptétété..
wikipedia
yo
Awọn ẹbun ninu Fisiksi, Kemistri, iwosan, Litireso, ati alafia kọkọ jẹ bibun ni 1901..
wikipedia
yo
Ẹ̀bùn Sveriges Riksbank ninu ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ okòwò ní ìrántí Alfred Nobel jẹ́ jímúlẹ̀ látọwọ́ Sveriges Riksbank ní ọdún 1968 ó sì kọ́kọ́ jẹ́ Bíbùn ní ọdún 1969..
wikipedia
yo
Bótilẹ̀jẹ́pé èyí kìí ṣe ẹ̀bùn Nobel gangan, ìkéde àti ìfifún rẹ̀ ń ṣẹlẹ̀ nígbà kan náà mọ́ àwọn ẹ̀bùn yoku..
wikipedia
yo
Ẹ̀bùn kọ̀ọ̀kan jẹ́ dídámo ní pàápàá fún iṣẹ́ wọn.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo