cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ìjàmbá sí ojú lè fà àìríran tàbí ìsọ̀rọ̀ pẹ̀lú Ian àtìàwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Etí jẹ́ ẹ̀yà ara, èyí tí ènìyàn àti ẹranko fi ń gbọ́ ọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Eniyan ati ẹran ọ̀sìn, (tí òyìnbó ń pè ní “Mámma") ní etí meji..
wikipedia
yo
A lè pín etí sí ẹ̀yà mẹ́ta; etí ìta, etí àárín àti etí inú, àwọn ẹ̀yà mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí ń ṣiṣẹ́ papọ̀ láti mú kí ènìyàn tàbí ẹranko gbọrọ..
wikipedia
yo
ijamba si eti (paapaa ju lọ; Ilu eti) le fa àìgbọràn tabi iṣoro pẹlu ọrọ gbigbọ́.Awọn itọkasieti..
wikipedia
yo
Ọkọ̀-ayára òfúrufú Atlantis tí ó ti lọ sí inú ofurufu lati nǹkan bi ọ̀sẹ̀ meji ni ó padà sí ilé ayé ní Edwards Air Base, California, U.S.A..
wikipedia
yo
gbogbo àwọn mejeeje tí wọ́n wà ninu rẹ̀ ni wọ́n bá a dé..
wikipedia
yo
Ọjọ́ márùndíndín (195 Days) ni ó gbé ní ojú òfúrufú..
wikipedia
yo
Oun naa ni obinrin ti o rin ni oju ofurufu ju.itọkasisáyẹ́ǹsìlantis..
wikipedia
yo
Orísirísi orin ni àwọn Yorùbá máa ń kọ fún oríṣiríṣi nǹkan tàbí ìṣẹ̀lẹ̀..
wikipedia
yo
Yoòbá a máa kọrin kẹ́dùn, wọn a máa kọrin ṣayẹyẹ, wọ́n máa ń kọrin ṣe ìkìlọ̀, bẹ́ẹ̀ wọ́n sin máa ń kọrin bú ènìyàn..
wikipedia
yo
Yorùbá a máa forin rẹ̀ ọmọ lẹ́kún, wọ́n á máa forin kí oríkì ẹni, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Orin nínú ọdún ìbílẹ̀èrò àti ìgbàgbọ́ Yorùbá nípa àjọ̀dún ìbílẹ̀ àjọ̀dún ìbílẹ̀ jẹ mọ́ bíbọ òrìṣà kan tí àwọn olùsìn rẹ̀ fi ń wájú mọ́ra tàbí láti fi bẹ̀bẹ̀ tàbí san ẹ̀jẹ́ lọ́dọ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
Àjọ̀dún ìbílẹ̀ tún lè wà fún ìrántí aṣáájú tàbí akọni kan, bóyá tí ó tẹ ìlú kan dó, tàbí tí ó jagun kan láti gba àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀ lọ́wọ́ ọ̀tá tàbí lọ́wọ́ ibi tàbí ìjàǹbá kan, tàbí tí ó ṣe ohun mánigbàgbé kan tí wọ́n fi ń rántí rẹ̀ tàbí tí wọ́n fi ń ṣọpẹ́ fún un, tí wọ́n sì ti ipa bẹ́ẹ̀ sọ ọ́ di òrìṣà tí wọn yóò máa bọ, tí wọ́n yóò sì máa ṣe ẹ̀yẹ fún lọ́dọọdún tàbí lóòrèkóòrè..
wikipedia
yo
...Àgbálọgbábọ̀ lórí orin Yorùbáìwúlò orin Yorùbá YORÙbaàgbaìtàn lórí ọriniwúlò orin Yorùbá jẹ́ ọ̀nà kan pàtàkì tí ẹni tí ó kọrin fi ń gbé eré-ọkàn rẹ̀ jáde lórí ohun tí ń jẹ ẹ́ lọ́kàn, yálà nípa ọ̀rọ̀ ara rẹ̀, ọ̀rọ̀ ẹlòmíràn tàbí nípa ọ̀rọ̀ kan láwùjọ..
wikipedia
yo
ọ̀kọrin lè fi orin mú ìwúrí àti ìdùnú bá ara rẹ̀ tàbí ẹlòmìíràn..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí alóre láwùjọ, ọ̀kọrin tàbí òṣèré le fi orin gbé ẹ̀dùn ọkàn èrò àwùjọ síta, èyí tí ìbá máa fún ni ní ìnira tàbí ìtẹ̀mọ́lẹ̀ tàbí ìbànújẹ́ abẹ́nú, yálà láti ọwọ́ ìjọba tàbí àwọn aláṣẹ kan..
wikipedia
yo
Orin lè mú ni ṣapá ṣe ohun tí ó dàbí ẹni ṣòroó ṣe fún ni nígbà mìíràn..
wikipedia
yo
...Orin apaláàpalaorin àpàlà ÌfáàràOrin àpàlà jé òkan lára àwọn orin Yorùbá tí wọn jẹ́ gbajúmọ̀ ní agbègbè Ẹ̀gbá, Ìjẹ̀bú, Oyo, Ọ̀ṣun àti Ìgbómìnà..
wikipedia
yo
Orin àpàlà kò ní nǹkan án ṣe pẹ̀lú ẹ̀sìn, òrìṣà tàbí ìbò kan tí a mọ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Orin ìgbafẹ́ ni orin àpàlà....orin Fújì ÌfáàràOrin ìgbàlódé ni orin Fújì..
wikipedia
yo
Àwọn ohun díẹ̀ péréte ni a ó sọ̀rọ̀ lé lórí nínú orin yìí..
wikipedia
yo
A ó fi ẹnu ba ohun èlò orin Fújì, àwọn ọ̀kọrin Fújì ìṣàkóso àti kókó tí Fújì ń dalẹ̀ lórí..
wikipedia
yo
...Orin sákárà ìfáàrà ẹ̀dá ìtàn méjì ni a gbọ́ tí ó rọ̀ mọ́ bí eré sákárà ṣe bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀kan ni pé ní ìlú Ìlọrin ni sákárà ti bẹ̀rẹ̀ láti ọwọ́ àwọn Mùsùlùmí kan, kí a tó mú un wá sí Ìbàdàn lásìkò baálẹ̀ situ tí ó jẹ́ Olúbàdàn láàrín ọdún 1914 sí 1925..
wikipedia
yo
Ẹ̀dá ìtàn kejì ni pé eré kerekere ni ó pilẹ̀ eré sákárà láti ọwọ́ Abudu, tí ó jẹ́ ọmọ Yorùbá kan tí ó ń ṣe àtìpó ní ìlú bídàá ní ìpínlẹ̀ Naija..
wikipedia
yo
...Orin àgàn àwọn orin kan wà ní ilẹ̀ Yorùbá tí wọn n kú lọ..
wikipedia
yo
Ìlú tí ẹ̀sìn òkèrè bá ti gba ẹ̀sìn ìbílẹ̀ lọ́wọ́ wọn, dandan ni kí irú orin bẹ́ẹ̀ kú pẹ̀lú ẹ̀sìn tí wọ́n gbé jù sílẹ̀....Orin Were ÌfáàràÌtara àti ìtanijí nínú ẹ̀sìn Mùsùlùmí ni a gbọ́ pé ipilẹṣẹ eré ajíwéré, nígbà tí àwọn olùfọkànsìn kan máa ń lọ káàkiri àdúgbò ní ìdájí láti jí àwọn mùsùlùmí láti kírun àárọ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n kó lọ gìtá Alápòọtí Mo ní wọ́n bẹ̀rẹ̀ síí lọ Bánjọ..
wikipedia
yo
Àwọn ohun-èlò ìbílẹ̀ tí wọ́n tún mú wọ inú ère Jùjú ní Ggan, sákárà tàbí ọrun isà, gudugudu, agogo, àgídìgbo tàbí Molo..
wikipedia
yo
Àwọn ohun-èlò ìgbàlódé tí a mú wọnú èrè Jùjú ní Gìtá, ọ̀pọ̀ ìlú alásopọ̀ ti ẹnití máa ń lù, bongo, kọ̀nga, ẹ̀rọ gbohùngbohùn, Miki, Busita, Adiounu àti dùùrù afẹnu, nígbà kan rí..
wikipedia
yo
...Orin nínú ọdún ìbílẹ̀èrò àti ìgbàgbọ́ Yorùbá nípa àjọ̀dún ìbílẹ̀ àjọ̀dún ìbílẹ̀ jẹ mó bíbọ òrìṣà kan tí àwọn olùsìn rẹ̀ fi ń wájú mọ́ra tàbí láti fi bẹ̀bẹ̀ tàbí san ẹ̀jẹ́ lọ́dọ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
…Ìwé tí a yẹ̀wòỌmọniyì Ajíbóyè (2003) Ewì alohùn Yorùbá Orin MaỌ̀jọ̀gbọ́n Books, Ìlọrin..
wikipedia
yo
ISBN978-32402-3-4, ojú-ìwé 95-124.link Title YORÙàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Orin wèrè je orin itara ati ìtanijí ninu ẹ̀sin Musulumi ni a gbọ pe ipilẹṣẹ eré Ajiwere , nigba ti àwọn olùfọkànsìn kan máa n lọ káàkiri àdúgbò ní ìdájí lati ji àwọn mùsùlùmí lati kírun àárọ̀..
wikipedia
yo
...Ìgbàgbọ́ Yorùbá nípa àjọ̀dún ìbílẹ̀orin nínú ọdún ìbílẹ̀ọdún ìbílẹ̀èrò Yorùbá nípa àjọ̀dún ìbílẹ̀orin nínú ọdún ìbílẹ̀èrò àti ìgbàgbọ́ Yorùbá nípa àjọ̀dún ìbílẹ̀ àjọ̀dún ìbílẹ̀ jẹ mó bíbọ òrìṣà kan tí àwọn olùsìn rẹ̀ fi ń wájú mọ́ra tàbí láti fi bẹ̀bẹ̀ tàbí san ẹ̀jẹ́ lọ́dọ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìlú tí ẹ̀sìn òkèrè bá ti gba ẹ̀sìn ìbílẹ̀ lọ́wọ́ wọn, dandan ni kí irú orin bẹ́ẹ̀ kú pẹ̀lú ẹ̀sìn tí wọ́n gbé jù sílẹ̀....Ìwé tí a yẹ̀wòỌmọniyì Ajíbóyè (2003) ewì alohùn Yorùbá Orin Masáàtì Books, Ìlọrin..
wikipedia
yo
ISBN978-32402-3-4, ojú-ìwé 95-124.Ọmọniyì Ajíbóyèlink Title Yorubaorin..
wikipedia
yo
Orin Sakaraorin Sakara Ìfáàrà Ẹ̀da ìtàn méjì ni a gbọ́ tí ó rọ̀ mọ́ bí eré sákárà ṣe bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
...Àgànkan àgànorin àgàn àwọn orin kan wà ní ilẹ̀ Yorùbá tí wọ́n ń kú lọ..
wikipedia
yo
Ìlú tí ẹ̀sìn òkèrè bá ti gba ẹ̀sìn ìbílẹ̀ lọ́wọ́ wọn, dandan ni kí irú orin bẹ́ẹ̀ kú pẹ̀lú ẹ̀sìn tí wọ́n gbé jù sílẹ̀..
wikipedia
yo
wéréorin wéréorin wéré ÌfáàràÌtara àti ìtanijí nínú ẹ̀sin mùsùlùmí ni a gbọ́ pé ìpilẹ̀ṣẹ̀ eré ajíwéré, nígbà tí àwọn olùfọkànsìn kan máa ń lọ káàkiri àdúgbò ní ìdájí láti jí àwọn mùsùlùmí lati kírun àárọ̀..
wikipedia
yo
Ali Hassan Al-Majid tí wọ́n máa ń pè ní Chemical Ali tí ó jẹ́ ará ilẹ̀ tí ó jẹ́ ará ilẹ̀ dáwá Hussein ni wọ́n ti dájọ́ ikú fún ipa tí ó kó nítorí Ìpolongo tí ó ṣe tako àwọn Kurds ní 1988.ìgbésíayé..
wikipedia
yo
Sir William Lawrence Bragg Chch Obe Mc Frs (31 March 1890 – 1 July 1971) ni ó kéré jù nínú àwọn ẹni tí ó ti gba Nobel Prize títí di ọdún 2001..
wikipedia
yo
Ọmọ ọdún márùndínlọ́gbọ̀n ni ó jẹ́ nígbà tí ó gba Nobel Prize nínú Fisiksi ní ọdún 1915.Ìtọ́kasíàwọn ẹlẹ́bùn Nobel nínú Fisiksiàwọn ẹlẹ́bùn Nobel ará Britaniàwọn ẹlẹ́bùn Nobel ará Australia..
wikipedia
yo
Colin Maclaurin (1698 – 14 June, 1746) ni ojogbon ti o kere ju lọ..
wikipedia
yo
Ọmọ ọdún mọ́kàndínlógún ni nígbà tí ó di Ọjọ́gbom Matimatiìkì ni Marischa College ní Aberdeen ní Scotland ní ọgbọ̀n-ọjọ́ Oṣù Kẹ̀sán-an Ọdún Omatise..
wikipedia
yo
Leyin eyi ni o lo di ojogbon mátìiko ni Edinburgh ni Scotland ni 1725..
wikipedia
yo
Sir Isaac Newton ni ó ní kí wọ́n sọ ọ́ di ọ̀jọ̀gbọ́n níbẹ̀.ìgbésíayé..
wikipedia
yo
Tí o bá ti pọ́n o ma ń pupa, bí ọṣẹ n pọ́n lọsi ma mà tobi..
wikipedia
yo
wọ́n má ń pé tomato ní èso nítorí pé ó ní irúgbìn tó pọ̀..
wikipedia
yo
Ṣugbọn àwọn eniyan má ń pẹ́ tomato l’ágbà ni ẹ̀fọ́, wọ́n sì dẹ̀ má ń sè bí ẹ̀fọ́.Bí oúnjẹ tomato jẹ́ èso kan tí a fi máa ń se ọbẹ̀..
wikipedia
yo
Tí ó bá pọ́n tán, kìí pẹ́ rà nítorí náà, àwọn ọlọ́jà máa ń fẹ́ tètè ta á tán..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ Hausa ni gbígbé tomato wọ́pọ̀ si jù ni ilẹ̀ Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ọ̀gbìnàwọn ohun ọ̀gbìn jíjẹàwọn onjẹ..
wikipedia
yo
Eẹnukún Castleorúkọ mìíràn tí a ń pe egemẹ́ta Castle ní Danish egetyl Slot..
wikipedia
yo
Omi ipamọ igba ‘Renaissance' ti o wa nibẹ ni o dara jù ni ilu òyìnbó..
wikipedia
yo
Ìtàn Castle náà ti bẹ̀rẹ̀ láti nǹkan bíi Sétúrì Kẹrìnlá..
wikipedia
yo
Ẹni ti o ya aworan Castle naa ni Frands Brockenhuus ni 1554...
wikipedia
yo
Anthony Charles Lynton "Tony Blair (ọjọ́ìbí 6 May, 1953) jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Britani tó jẹ́ alákòóso àgbà orílẹ̀-èdè Ilẹ̀ọba ìṣọ̀kan ti Britani níńlá àti ìrẹdi Kaṣàtúnṣe láti ọjọ́ 2 May ọdún 1997 títí di ọjọ́ 27 June ọdún 2007.Ìtọ́kasí Blair Tony Tony
wikipedia
yo
James Gordon Brown (20 February, 1951) jẹ́ alákòóso Agba orile-ede Ilẹ̀ọba pẹ̀lú ti Britani níńlá àti ìrẹ́lándi àparíwá (United Kingdom of Great Britain and Northern Ireland) tele.Ìtọ́kasí àwọn ará Brigo..
wikipedia
yo
Ekánná ri bi iwọ ni ori ìka-owo tabi ìka-ẹsẹ̀ ọmọ eniyan.Sáyẹ́ǹsì..
wikipedia
yo
KAMẸRÚÙNÙ tàbí orílẹ̀-èdè òkẹrin ilẹ̀ KàKamẹrúùnù Kapàsí ní orílẹ̀-èdè asòlẹ̀ ní àrin ati apáwà Afrika..
wikipedia
yo
O ni Bode Mo Nàìjíríà ni iwoorun; Tsad ni ariwailaọrun; Orilẹ-ede olominira àpaarin Afrika ni Ilaọrun; ati Guinea Alagedemeji, Gabon, ati orile-ede olominira Ilẹ Alanko ní Gúúsùjiji..
wikipedia
yo
Ìwé-ìròyìn ni ìtẹ̀jáde ìròyìn wíwọ́pọ̀..Ìtọ́kasí àwọn irù amóhùnhùnìwé titẹiseròyìn..
wikipedia
yo
Omi jẹ́ ohun tí ó ṣe pàtàkì fún gbogbo ohun ẹlẹ́mìí..
wikipedia
yo
Omi ò lóòórùn, kò ní àwọ̀ àti bẹ́ẹ̀ ni kò ní adùn, ó jẹ́ èròjà tó pọ̀ nínú afẹ́fẹ́, ilẹ̀ àti okùn..
wikipedia
yo
Omi tún wà nínú ara gbogbo ohun ẹlẹ́mìí tí ó má ń yòrò..
wikipedia
yo
"Omi" ni oruko àdàpè ti awon Geesi n pee ni H20 ni ipo ṣiṣan..
wikipedia
yo
Ní ipò yìí omi lè di ohun tí ń ro bíi òjò, tabi ohun tí afẹ́fẹ́ ń gbé bí kùrukùru..
wikipedia
yo
A lè rí ìkùukùu nígbà tí omi ati omi dídì bá ṣù pọ̀ lójú sánmà..
wikipedia
yo
Nígbà tí omi náà bá ṣèpínyà, omi dídì òníkírísítálì lè já bọ́ gẹ́gẹ́ bí yìnyín..
wikipedia
yo
Omi máa ń yí ipò rẹ̀ ní ipele kọ̀ọ̀kan ti ìyípoyípo omi..
wikipedia
yo
3300 BCE to 1300 BCE) dagbasoke lẹ́bàá odò Indus àti àwọn odò míì tí ń ṣàn láti òkè Himalaya..
wikipedia
yo
Wọ́n kọ́ ìlú Róòmù ìgbàanì ní bẹ̀rẹ̀ odò taìbá tó wà lórílẹ̀-èdè Itali..
wikipedia
yo
Awon igboro ilu nla igbalode bii Eko, Lọndọnu, Tokyo, Parisi, Montreal, Rotterdam, Shanghai, pàtàkì CFR, New York ati Sitan ti gbooro lápá kan nitori won lanfaani si omi..
wikipedia
yo
Àwọn Erékùṣù tó ní Èbúté Aláìléwu, gẹ́gẹ́ bí Singapore, ti dọlọ́rọ̀ nítorí ìdí ohun bákan náà..
wikipedia
yo
Ní ẹkùn ilẹ̀ aláìtó omi gẹ́gẹ́ bíi apá Àríwá Áfíríkà àti ilẹ̀ Lárúbáwá, àǹfààní omi tó ṣeé mú tí ń ṣe kókó fún ìdàgbàsókè ènìyàn.Ìlera àti ìbàyíkájẹ́ “Omi tó ṣeé mu” là ń pe omi tí kò lárùn nínú..
wikipedia
yo
Bí omi kò bá ṣeé mu, àá sè é, tabi kí á sẹ́ ẹ kí á tó mu ún..
wikipedia
yo
Nǹkan bí àádọ́ta ọ̀kẹ́ lọ́nà 660 ènìyàn wà tí kò láǹfààní sí omi tó ṣeé mu.Omi tí a ò le mu ṣùgbọ́n tí a le lò ó láti wẹ̀ là ń pè é ní ''Omi tí kò léwu’’ tàbí ‘’Omi tó dára’’..
wikipedia
yo
Kílóríìní ni wọ́n máa ń fi sínú omi kí a lè lò ó láti wẹ̀ tàbí mu ún.Ìgbàgbọ́ àti ẹ̀sìn nípa omi nínú ẹ̀sìn púpọ̀, wọ́n ka omi sí ohun mímọ́..
wikipedia
yo
Ní ẹ̀sìn Kírísítì, wọ́n máa ń ṣe ìrìbọmi gẹ́gẹ́ bíi ìyàsímímọ́..
wikipedia
yo
Òrìṣà Ọ̀ṣun àti Yemọja jẹ́ obìnrin, ṣùgbọ́n Olókun ó jẹ́ obìnrin tàbí ọkùnrin..
wikipedia
yo
Orúkọ ọ̀dọ̀ Ọ̀ṣun tó wà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ni wọ́n fàyọ lati orúkọ òrìṣà yẹn..
wikipedia
yo
Ọ̀dọ̀ Ọ̀ṣun ni àwọn olùjọ́sìn Ọ̀ṣun máa ń ṣayẹyẹ ọ̀súnlé Òṣogbo lọ́dọọdún.Àwọn ìtọ́ka síomi..
wikipedia
yo
Martin Luther King, Jr.(January 15, 1929 – April 4, 1968) je eni owo, alákitiyan ọmọ orile-ede Amerika,bee ni o si je olori egbe-ijinde fun eto omo-awujo ni ile Amerika..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí oniwasu Ìjọ Onítẹ̀bọmi, King di alákitiyan fún ètò ará-ìlú ní ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀.Ìgbà èwe rẹàwọn ìtọ́ka síàwọn Ọjọ́ìbí ní 1929àwọn ọjọ́aláìsí ní 1968àwọn ara Américo ọmọ Áfríkà Américo Ara agboAmégbọ̀n Ara ohunkóhunwọ́n Nobel ara Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Malcolm X (; May 19, 1925 February 21, 1965), àbísọ Malcolm Little bákan bi el-Hajj Malik el-Shabacasal Kaka jẹ́ ọmọ ilẹ̀ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí àwọn ọmọ Áfríkà Amẹrika..
wikipedia
yo
Nelson ìdákọ̀ró Mandela (; ọjọ́ kejidinlogun oṣu keje ọdún 1918 – ọjọ́ karun-un Oṣu kejila ọdun 2013) jẹ aare guusu Afirika lati odun 1994 titi di odun 1999, bẹẹ si ni oun ni aare guusu Afírík[s akọkọ to je eni adibo ninu idibo-yani toṣèlú ara ilu asoju yányán..
wikipedia
yo
Kí o tó di Ààrẹ, Mandela jẹ́ alákitiyan olódi-àpartheid, àti olórí Ummainto we Sizwe, apá adigun ìgbìmọ̀ aṣòfin ọmọ Orílẹ̀-èdè Áfíríkà (AN)..)..
wikipedia
yo
Lọ́dún 1962 ó di ẹni afọ̀ilẹ̀àti wọn sì dá lẹ́bi ìkà ọ̀tẹ̀ àti àwọn ẹ̀sùn mìíràn, wọ́n sì rán an lẹ́wọ̀n gbére..
wikipedia
yo
Mandela lo ọdun mẹtadinlọgbọn (27) ni ẹwọn, o lo opo ọdun yii ni Robben Island..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn jíjọ̀wọ́ rẹ̀ kúrò lọ́gbà ẹ̀wọ̀n ní ọjọ́ 11 oṣù kejì ọdún 1990..
wikipedia
yo
Mandela siwaju ẹgbẹ́ òṣèlú rẹ̀ ninu àwọn ìfọ̀rọ̀rí tó fa òṣèlú ÀwaáÀwaárawa ti gbogbo ẹ̀yà tí ó wáyé ní ọdún 1994, tó sì di ààrẹ orílẹ̀ èdè Gúúsù Áfíríkà láti ọdún 1994 títí di 1999..
wikipedia
yo
Ó sì ṣokùnfà ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ní Gúúsù Áfríkà, bákan náà ni a tún mọ Mandela sí Madiba, oyè ẹyẹ tí àwọn alàgbà ìdílé Mandela ń lọ.Mandela ti gba ẹ̀bùn tó pọ̀ ju 250 lọ láàárín ogójì ọdún, nínú wọn ni ẹ̀bùn àlàáfíà Nobel 1993.Igba ewé Nelson Mandela jẹ́ ọmọ ẹ̀ka kékeré ìran ọba thembu dynasty, tó ń jọba ní agbègbè transkékéké ní ìgbèríko Cape Gúúsù Áfíríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n bí i ní Mvezo, abúlé kékeré kan tó sún mọ́ agbègbè Umtata, tó jẹ́ olú-ìlú transkéké..
wikipedia
yo
Baba ńlá baba rẹ̀ ni Ngubengcuka tó jọba gẹ́gẹ́ bí inKosi enaklú tàbí Ọba àwọn thembu ṣáájú kó tó kú ní ọdún (1832)..
wikipedia
yo
Ìkan nínú àwọn ọmọkùnrin ọba ọ̀hún ló ń jẹ́ Mandela, ni baba nlá rẹ àti ibi ti orúkọ ìdílé rẹ ti wá..
wikipedia
yo
Síbẹ̀ nítorí pé ó jẹ́ ọmọ inKosi's látọ̀dọ̀ ìyàwó ìran Ixhiba (ìyẹn “Ìdílé Olówó O"), àwọn ọmọ-ọmọ ẹ̀ka ẹbí ọba rẹ̀ kò lè gorí ìtẹ́ ní thembu.Bàbá Mandela ni Gaddi Henry MPd Swayi..
wikipedia
yo
ṣùgbọ́n nítorí àìgbọràn sí ìjọba amúnisìn lẹ́nu, wọ́n yọ póHakantéSwa kúrò ní ipò oyè rẹ̀ wọ́n sì kó ẹ̀bi rẹ̀ lọ sí Qfínù..
wikipedia
yo
Síbẹ̀, MPHakantéSwa kò kó ṣàìjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ àdákúmọ́ inKosi, bẹ́ẹ̀ sì ni ó kópa gidi láti rí i pé Jongin dáLindtan gun orí ìtẹ́ thembu..
wikipedia
yo
DaLindyèbọ́ san Ore yi paa fun MPDentSwa nipa gbigba Mandela sọdọ bi ọmọ nigba ti MPDentr ku..
wikipedia
yo