cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Eko ninu lost, lock-nah ninu the Mummy returns, NYkwana Sobobo ninu the bourne identity, heavy duty ninu g.I..
wikipedia
yo
Laurence John Fishburgne III (tí a bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n Oṣù Keje Ọdún 1961) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O ti gba ami-eye Emmy Award ni ẹ̀mẹ́ta ti ati ami eye Tony Award..
wikipedia
yo
O gbajumọ fun ipa rẹ gẹgẹ bi Morjinnú ninu The matrix series (1999-2003), Jason "Furious" Styles ninu ere John Singnti akori re je Zhe n the Hood (1991), Tyrone "Mr..
wikipedia
yo
Clean" Miller ninu eré Francis Ford Coppola ti akori rẹ̀ jẹ́ Apocalypse now (1979), àti gẹ́gẹ́ bí "The bowe King" nínu John Saore Film series (2017-titi í di ìsinsìnyí).Fún ipá rẹ gẹ́gẹ́ bí ike Turner nínú what's Love Got To Do with It (1993), Fish Wa lára àwọn tí wọ́n yàn pé ó tó sí àmì ẹ̀yẹ Academy Award for Best Actor..
wikipedia
yo
O tun gba ami-eye Tony Award for Best featured Actor in a Play fun ipa re ninu Two Trains running (1992), ati Emmy Award for Outstanding Guest Actor in a Drama series fun ipa rẹ ni Tribeca (1993).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ọmọ ọba Joel Olaniyi Òntọ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí bàbá Asa, jẹ́ ọmọ bíbí orile-ede Naijiria àti Kánádà, ó jẹ́ akọ ewi, olugbohunsafefe, oníjíṣẹ́ Ara-ẹni, àjíjírere, rere olùpolongo ati Olugbẹ̀ asạ̀ àti iṣẹ́ Yorùbá. Àyè kò bí Olaniyi ní Ìpínlẹ̀ Kwara ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní 27 January, 1984 níbi tí ó ti lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama àti girama kí ó tó lọ sí orílẹ̀-èdè Canada láti lọ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Òntọ̀ tí ó jẹ́ Ọmọọba nígba sí gbígbé asa Yorùbá ṣùgbọ́n lọ́ka-já àgbáyé, paá paá jùlọ bí ó ṣe má ń wọ aṣọ ìbílẹ̀ ìbílẹ̀ tí ó sì ń lo gbogbo ohun elo ìbílẹ̀ Yorùbá láti fi pàtàkì asa Yorùbá hàn ipa rí..
wikipedia
yo
Óyàtọ̀yé jẹ́tọ àṣà òun ìgbéga Yorùbá láti kékeré lati ara bàbá rẹ Oloye Titus Oyàtọ̀ye titiloyè tí ó ti dolóògbé..
wikipedia
yo
Iya rẹ Cikún Oyàtọni rẹ o ríran ṣakiyesi wipe ina asa ati iṣẹ Yoruba ti n jo àjórẹ̀yìn, eyi ko si bójúmu, aibikita si igbega asa oun iṣe Yoruba le ṣàkóbá fun lati ròkun ìgbàgbé..
wikipedia
yo
Èyí ni ó múmú láyà rẹ̀ tí ó fi ń gbé àdá Yorùbá lákò́n..
wikipedia
yo
Ìfẹ́ rẹ̀ sí èdè Yorùbá ni ó mú kọsẹ̀ nípa ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ láti lè má polongo ohun iná àjogúnbá Yorùbá lórí afẹ́fẹ́..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún [[ewì][ kíké, rárà sísun, ìjálá, ẹkún ìyàwó sísun àti oríkì kíké.Láti le mú ẹ̀rọ àti àlá rẹ̀ ṣẹ, ó gbéra lọ sí orílẹ̀-èdè Canada láti lọ kẹ́kọ̀ọ́ tí ó sì ń ṣiṣẹ́ mọ́..
wikipedia
yo
O lo ile eko Red River College, ati Academic College ti awon méjè wa ni agbegbe Winnipeg ni ilu Canada, o ko eko nipa eto Iṣiwa (IMMI SDOS) ni Ashton College British Columbia Canada..
wikipedia
yo
O ti sise pelu ile-ise aabo ''Impact security laarin odun 2013 si 2015, bakan naa ni o ti sise pelu St Amant laarin odun 2013 si 2020 ni orile-ede Canada..
wikipedia
yo
O jẹ àárẹ̀ àti olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ ti à n pè ni àṣà Day Worldwide Inc..
wikipedia
yo
Canada, ti n ṣe ìgbẹ́ láruge asa Yoruba kakiri agbaye, oun si tun ni oludasile ati alamojuto asa Day Museum ni Canada.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
John Peter SARSgaard (; tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1971) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O ṣere fun igba akọkọ ninu ere Dead Man Walking ni ọdun 1995..
wikipedia
yo
O tun ṣere ninu fiimu Independent ti akọle rẹ jẹ another day in Paradise ati ninu Desert Blue..
wikipedia
yo
Ní ọdún kan náà, SARSgaard kópa Raoul nínú eré The Man in the iron Mask (1998)..
wikipedia
yo
SARSgaard padà di gbajúmọ̀ nígbà tí ó kópa John lọtter nínu eré Boys Don't Cryne (1999)..
wikipedia
yo
Fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Charles Lane nínu eré Shattered Glass, won yan SARSgaard mọ́ ara awon ti o tòsí ami-eye Golden Globe Award for Best Supporting Actor..
wikipedia
yo
O gbajumọ fun ipa rẹ ninu awọn ere Green Lantern (2011), Knight and Day (2010), the Magnificent Seven (2016) ati The Batman (2022)...
wikipedia
yo
Àwọn eré míràn tí ó ti farahan ní gẹ́gẹ́ bi John Winchester ní eré The Cw tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ supernatural (2005-2007; 2019), gẹ́gẹ́ bi Denny Duquette nínu eré ABC tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Grey's Anatomy (2006-2009), gẹ́gẹ́ bi Jason Crouse ninu eré CBS tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ gẹ́gẹ́ bi The Good Wife (2015-2016), aláwàdà nínú Watchmen (2009), àti nínú àwọn eré bi p.S I Love You (2007), The Llosers (2010), Red Dawn (2012),ati Rampage (2018).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Hilarie ros Burton (tí a bí ní ọjọ́ Kínní Oṣù Keje ọdún 1982), tí àwọn mìíràn mọ̀ sí Hilarie Burton Morgan, jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O ti fi igbaati je olótùú fun eto MTV tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Total request Live, ó ṣeré gẹ́gẹ́ bi péyton Sawyer nínu eré Dmàá àti CW tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ One Tree Hill (2003-2009
wikipedia
yo
Lẹ́yìn one tree Hill, Burton ṣeré ninu our very own, solstice, ati the list..
wikipedia
yo
O tun ko ipa Sara Ellis ninu ere White collar (2010-2013), Dr..
wikipedia
yo
Lauren Boswell ninu ABC Medical Drama Grey's Anatomy (2013), Molly Dwes ninu ere ABC pelu akole Forever (2014), ati gege bi Karen Palmer ninu Fox, bakan naa o farahan ninu Lethal weapon (2016)..
wikipedia
yo
Burton jẹ́ ara àwọn olóòtú ètò Drama Queens òun pẹ̀lú Sophia bush àti Bethany Joy Lenz.àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Amy Lou Adams (ti a bi ni ojo ogun osu kejo odun 1974) je osere omo orile ede Amerika..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún àpépe àti ìtara nínú àwọn eré tí ó ma n ṣe, ó wà lára àwọn òṣèrébìnrin tí wọ́n ń san owó fún jùlọ ní àgbáyé..
wikipedia
yo
O ti gba ọpọlọpọ ami-eye, ami-eye bi Golden Globe Awards meji, won si yan ni emefa mo ara awon ti o to si ami eye Academy Awards, ni emeje mo ara awon ti o to si British Academy Film Awards, ati ni ẹ̀mejì mo ara awon ti o to si Primetime Emmy Awards.Adams bẹrẹ gege bi onijo ni gbọ̀ngàn onijo laarin odun 1994 si 1998, o si bẹrẹ iṣẹ osere nigba akoko ninu ere drop Dead Gorntian (1999)..
wikipedia
yo
Láti ìgbà náà, ó ti ṣeré nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré bí "mean Girl", Catch Me If You Can (2002), Junebug (2005) - èyí tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Award fún.àwọn eré míràn tí ó ti farahan ní EnChanted (2007), Yyo (2008), The Fidu (2010), The Master (2012), American Huàmì (2013), Big Eyes (2014), Arrival (2016), sharp objects (2018), Vice (2018)..
wikipedia
yo
Laarin odun 2017,o ko ipa lios Lane ninu awon ere DC extended Universe.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Cilian Murphy ( ; ti a bi ni ojo karuntàlélógún osu karun odun 1976) je osere omo orile ede Ireland..
wikipedia
yo
O ṣere fun igba akọkọ ninu ere ndanda Walsh Ltì akori rẹ jẹ Disco pigs ni ọdun 1996..
wikipedia
yo
Awon ere miran ti o ti farahan ni 28 Days later (2002), ninu Intermission (2003), Red Eye (2005), the wind that sha the barley (2006), Sunshine (2007)..
wikipedia
yo
O ṣere ninu ere Breakfast on Pluto (2005), eyi ti o mu ki wọn yan kun ara awon ti o to si Golden Globe Award.Murphy bẹrẹ si n sise pelu Christopher Nolan ni odun 2005, o ko ipa Dr..
wikipedia
yo
Jonathan Crane / SCaredi nínu eré The Dark Knight Trilogy (2005-2012), nínú Inception (2010), Dunkirk (2017), àti gẹ́gẹ́ bi J..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ sí nígbà tí ó ṣeré gẹ́gẹ́ bi Tommy Shelby nínu eré BBC tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ péa blinders (2013-2022) àti nígbà tí ó ṣeré nínú a Quiet Place Part II’’ (2020).àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Aaron Edward EckHartley (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kẹta ọdún 1968) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n bí ní Cuperníà, California, EckHartley lọ sí orílẹ̀ èdè United Kingdom nígbà tí ó wà ní èwe..
wikipedia
yo
O bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣeré nígbà tí ó ṣì wà ní ilé ìwé kí o tó lọ sí Australia..
wikipedia
yo
O fi ile-iwe High School kale lai gba iwe eri sugbon o pada gba ami-eye diploma, o si kawe gboye ni Yunifasiti Brigham Young (Reo) ni Utah, U.S., ní ọdún 1994 pẹ̀lú àmì-ẹ̀yẹ Bachelor of Fine Arts nínú eré ṣíṣe..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó sì jẹ́ ọmọ ilé ìwé ní Bemba, Eck pàdé adarí eré Neil lábútẹ́..
wikipedia
yo
Ọdún márùn-ún lẹ́yìn ìgbà náà, EckHartley nínú eré Labúbú tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Black Comedy ní in the company of Men (1997), ó sì padà farahàn nínú eré mẹ́ta míràn tí Neil darí..
wikipedia
yo
EckHartley gbájúmọ́ sí nígbà tí ó kó ipa George nínú eré erin Brockovich (2000), àti ní 2006, wọ́n yàn mọ́ ara àwọn tí ó tọ́ sí àmì ẹ̀yẹ Golden Globe fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Nick NyLorr nínú Thank You for Smoking..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2008, ó ṣeré nínu eré Christopher Nolan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Batman The Dark Knight gẹ́gẹ́ bi Harvey dent / Two-Face.Ní ọdún 2019, ó ṣeré nínu eré Roland Emmerich tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Midway...
wikipedia
yo
GuOsa jẹ́ ìfọ̀rọ̀wérọ̀ tí a kọ ní ìpilẹ̀ṣẹ̀ látọwọ́ Alex ìgbínEweka ní 1965..
wikipedia
yo
A ṣe é láti jẹ́ àkópọ̀ àwọn èdè ìbílẹ̀ Nàìjíríà àti láti sìn gẹ́gẹ́ bí èdè kan sí ìwọ oòrùn Áfíríkà.Ìwé àkọsílẹ̀ Okafor, Juddl-Leonard (20 March 2016)..
wikipedia
yo
"Hausa, Igbo and Yoruba are the triPod of guOsa language - ìgbíneweka"
wikipedia
yo
The Complete Dictionary of GuOsa language 2nd Revised edition..
wikipedia
yo
"50 uniAbuja Students undergo guOsa language Training"
wikipedia
yo
Morena Silva de Vaz Ṣetta BacCarin (; ti a bi ni ojo keji osu kefa odun 1979) je osere omo orile ede Amerika..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìnára Serra nínú eré Firefly àti serekàyéfì, gẹ́gẹ́ bí Vanessa nínú eré Deadpool, Jessica Brody nínú eré Showtime tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Homeland, Dr..
wikipedia
yo
Leslie "Lee" Thompkins nínú eré Foxti àkòrí rẹ̀ jẹ́ Goham, àti gẹ́gẹ́ bí Elena Fedèròva the Endgame..
wikipedia
yo
Fun ipa rẹ ninu Homeland, o wa lara awọn ti wọn yan pe o tọ si okan lara awọn ami ẹyẹ Primetime Emmy Award ni ọdun 2013.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Malin Maria Saraman (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá Oṣù karùn-ún Ọdún 1978) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Sweden..
wikipedia
yo
Ní àárín ọdún 2003 sí 2004, ó kú nínú eré The Upian Society (2003) àti Harold & Kumar gọ̀ tó White Castle (2004–
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó farahàn nínu eré Hbo tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ The Covback (2005), ó farahàn nínu àwọn eré bí The heartbreak Kid (2007), 27 dresses (2008), the invpts (2007)..
wikipedia
yo
O ko ipa silk kaalágbèékáre II ninu ere watchmen (2009), eyi si mu ki won yan an mo ara awon ti o to si ami eye Saturn Award ni odun 2009, Saraman sere ninu The Ppsal ati Couples Rein..
wikipedia
yo
Laarin odun 2010 si 2016, o ṣere ninu ere awada adult Harto ti akole re je Childrens Hospital..
wikipedia
yo
Awon ere miran ti o ti farahan ni WWSTst, Rock of Ages, Trocado wife (2013-2014), I'll see You in my Dreams (2015), Rampage (2018) ati ninu Billions gege bi lara Axelrod.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
William John Neeson (born 7 June 1952) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Northern Ireland..
wikipedia
yo
O ti gba ọpọlọpọ oríyìn bi ami-eye golden Globe awards mẹta ati Tony Awards meji..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2020, ó jẹ́ ipò keje nínu àwọn òṣèré tí The Irish Times sọ wípé ó gbajúmọ̀ jùlọ..
wikipedia
yo
Wọ́n fún Neeson ní ipò Officer of the Order of the British Empire (ọbẹ̀) ní ọdún 2000.Ní ọdún 1976, Neeson darapọ̀ mọ́ Lyric Pprs' Theatre ní ìlú Belfast fún ọdún méjì..
wikipedia
yo
Awon ere ti o ti koko farahan ni ExCaliBur (1981), The Bounty (1984), The Mission (1986), the Dead Pool (1988), and Husband and Wives (1992).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
TbereDeus si ninu Shazam! (2019) ati Shazam! Fury of the Gods (2023), ati Gẹgẹ bi John ninu Cruella (2021)...
wikipedia
yo
TẹWAOG Derek Morrison (ti a bi ni ojo kerindinlogbon osu kejila odun 1960) je osere omo orile ede New Zealand ti o gbajumọ ni orile ede fun ipa rẹ gege bi Dr..
wikipedia
yo
Ipa re gege bi jake "The Muss" heke ninu ere once were Warriors ti o jade ni odun 1994 ati what becomes of the broken rot? ti o jade ni odun 1999.Ni awon orile ede miran Morrison gbajumo fun ipa re Jango fett ati Bóbá ninu awon ere star wars..
wikipedia
yo
Òun ni ó kọ́kọ́ kó ipa Jango nínu eré Attack of the Clones tí ó jáde ní ọdún 2002..
wikipedia
yo
Awon ere miran ti Morrison ti sere ni the Empire strikes back, gege bi Bóbá ninu the Mandalorian (2019–titi di ìsinsìnyí), The Book of Bóbá Fett (2021-2022), Echo 3, gege bi Tom Curry ninu AquAman (2018), The flash ati AquAman and the lost Kingdom...
wikipedia
yo
Carla Gugino ( ; tí a bí ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹjọ Ọdún 1971) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó farahàn nínú eré Troop Beverly Hills (1989) àti This Boy's Life (1993), ó gbajúmọ̀ fún ipá rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ingrid Cortez nínú eré Spy Kids (2001-2003), Rebecca Hutman nínú Night at the Museum (2006), Laurie Roberts nínú American Gangster (2007), Ibie..
wikipedia
yo
Alex Friedman nínú race tó Witch Mountain (2009), Sally Jupiter in Watchmen (2009), Dr..
wikipedia
yo
Vera gorski ninu Sufker Punch (2011), Amanda Popper ninu Mr..
wikipedia
yo
Popper's Penguins (2011), Emma ràgàjì ninu San Andreas (2015), ati Gẹ́gẹ́ bi Jessie Burlingame ninu Gerald's Game (2017).Guce tún kó ipa nínú eré the Karen Sisco (2003), Thnnhold (2005-2006), The háúnting of Hill House (2018), nínú Jett (2019), Ó sì tún farahàn nínú The háúnting of Bbly Manor (2020)...
wikipedia
yo
Yusuf Kronde lulẹ̀ (10 April 1912 – 21 January 1985) fìgbà kan jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti orílẹ̀-èdè Uganda, àti òṣìṣẹ́ ìjọba tó sìn gẹ́gẹ́ bí i Ààrẹ Uganda Kẹrin láàárín oṣù kerin àti oṣù kẹfà Ọdún.Ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bí Yusuf lulẹ̀ ní 10 Aprilm ọdún 1912 ní Kampala..
wikipedia
yo
O kawe ni King's College bùdó (1929-34), Makerere University College, Kampala, ní ọdún (1934-36), Fort hare University ni Alice, South Africa (1936-39) ati ní University of Edinburgh..
wikipedia
yo
Ẹlẹ́ṣin mùsùlùmí ní tẹ́lẹ̀ kí ó tó gbèsin kirisiteẹni nígbà tó wà ní King's College bùdó.Ní ọdún 1947, lulẹ̀ fẹ́ Hannah námùli Wmálà ní ilé-ìjọsìn Kings College bùdó, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ bí i olùkọ́, ti arabìrin náà sì jẹ́ olórí àwọn obìnrin.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Juan dé o’ojú y ó’Ryan tí a bí ní ọjọ́ 30 oṣù July, ọdún 1762, tó sì ṣaláìsí ní ọjọ́ 8 oṣù October, ọdún 1821) jẹ́ ológun ọmọ ilẹ̀ Spain tó tú n jẹ..
wikipedia
yo
Oun si ni Viceroy ile Spain to kẹ́yìn, lati ojo 21 Oṣu July, ọdun 1821 wo ọjọ 28 Oṣu September, ọdun 1821 lásìkò ogún ominira ti Mexico.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Agustin de Ituīji (27 September 17 July July 1824), ti orukọ rẹ ni kikun jẹ Agustin Cosmeme damian de Ituīru y Aram ti won pada pe ni Emperor Agustin I of Mexico jẹ ologun ti ile Spain..
wikipedia
yo
José Mariano Micheleña (July 14, 1772 – May 10, 1852) jẹ́ ààrẹ Ìlú Mexico tẹ́lẹ̀ rí, láti Oṣù kẹrin ọdún 1823 wọ oṣù Kẹwàá ọdún 1824.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
José Miguel acetylaládùúgbò aleman (January 14, 1756 Most Like in Mexico City – April 22, 1830 in Mexico City) jẹ́ ológun ti ilẹ̀ Spain tó kó ipa ribiribi nínú ìgbòmìnira i lù náà..
wikipedia
yo
oyèkúnlé Ayinde "Kunle" olukọ je ọmọ Britain to tun tan mo ile Naijiria je onimo ero, to si tun je ojogbon ti Cadence Design systems professor ni Stanford School of Engineering, ojogbon ninu imo sìpẹ̀ Engineering ati Computer Science ni Stanford University, ati oludari laabu Stanford pervvebùkún Paralle.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Winston wọlẹ̀ Sobọ̀yè tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí “wọlẹ̀” jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́nsì ti orílẹ̀-èdè America, tí àwọn òbí rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Yorùbá..
wikipedia
yo
Oun ni adele won ni Worcester Polytechnic Institute.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Deji Akinwándé jẹ́ ọmọ orílẹ̀ Naijiria tó sì tún tan mọ́ ilẹ̀ America..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ojogbon nínú ìmọ̀ North and computer Engineering to sí tún ní ìkẹrin mọ́ mateU Science Science ní University of Texas at Austin..
wikipedia
yo
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Presidential Early Career Award for Scientists and Mainmónì ní ọdún 2016 láti ọwọ́ Barack Obama..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ-ẹgbẹ American physical Society, African Academy of Sciences, mateU Research Society (Mrs), ati Vẹe.àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
John olùṣeun dàbíri jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tó tún tan mọ́ ilẹ̀ America..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ tó ń rí sí ọkọ̀ òfúrufú, òun sì ní ọ̀jọ̀gbọ́n alága ní California Institute of Technology (Caltech).àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Alexander Obiẹfọka ẹnukora Animalu (ti a bi ni 28 August 1938) jẹ ọ̀mọ̀wé ti orilẹ-edeNaijiria, to si jẹ ojogbon agba ti imo physics ni University of Nigeria, Nsukka.O gboye BSc (London), M.A..
wikipedia
yo
(canbb.)ati PhD (Ibadan), FAs, NLYM, IÔM.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
lọlá (Lọ́la) Eniola-Adéfẹ̀sọ̀ jẹ́ onímọ̀ Chemical Ṣebíeer àti ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Chemi Engineering, BioMedical Engineering, àti Mamolecular Science àti Engineering ní University of Michigan..
wikipedia
yo