cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Eniola-adefẹ̀sọ̀ jẹ́ ọ̀kan lára àwọ olùdásílẹ̀ àti onímọ̀ sáyẹ́nsì àgbà ní àṣàlyxa Bio..
wikipedia
yo
She was going to attend medical school but became interested in Chemi Engineering.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ndui èkéK (ti a bi ni July 1975) je onisowo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun ni oludasile First Atlantic semiConductors & Microeléjì..
wikipedia
yo
Ni odun 2020, ile-ise iwe-iroyin The Guardian (Nigeria) to o po mo okan lara awon ogofa omo Naijiria to n sise ribiribi.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Unoma Ndili Omoke je onimo ero Kọmputa ati onisowo..
wikipedia
yo
Okora ṣe ìdásílẹ̀ working to advance African women ní ọdún 2007, wàáw is a 501(c) not-for-profit which wáyétes stem education to African women..
wikipedia
yo
èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ àìlérè lórí tó ń ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ètò-ẹ̀kọ́ àwọn obìnrin nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ, sáyẹ́nsì àti ìṣirò..
wikipedia
yo
They have over one hundred volunteer University Omils and reach several thousand girls a year..
wikipedia
yo
Òun ni adarí agbá ní Herbal 106 àti Fairview dátà Techologist..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ karun-un ti Frank Nwachukwu Ndili, ẹni tó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ tó máa ní ìmọ̀ nípa Aapaclear physics, tó sì tún jẹ́ Gíwá keje ti University of Nigeria, Nsukka.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Philip Emeagwali (tí a bí ní 23 August 1954) jẹ́ Onímọ̀ ẹ̀ro ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O gba ami-eye ti Gordon Bell Prize ni 1989.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
E.Tunde Odekuku (ti orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́, Emanuel Olatunde Alaba Olanrewaju Odeku, ni a bí ní ọdún 1927, sí Ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó sì ṣaláìsí ní ìlú, London, ní ọdún 1974) jẹ́ oníabẹlọpọlọ àkọ́kọ́ tó máa jẹ́ ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
United States ni o ti gbẹ̀kọ́, o si fi ìdí iṣẹ́ yìí sọlẹ si ilẹ̀ Africa.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Chidi Chike Achebe (tí a bí ní ọjọ́ 24 Oṣù May, Ọdún 1967) jẹ́ Oníṣègùn..
wikipedia
yo
Oun ni Alaga ati oludari agba fun Aide (African Integrated Development Enterprise)..
wikipedia
yo
Oun ni ọmọ kẹta ti Chinua Achebe, ìyẹn òǹkọ̀wé tó kọ àwọn ìwé bí i Things Fall Apart (1958); “No longer at ease" (1960); àti “Arrow of God" (1964).Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Charles Nohuoma Rotimi (tí wọ́n bí ní ọdún 1957) jẹ́ olùdarí àgbà ní National Institutes of Health (nih) ó ṣe ìdásílẹ̀ African Society of Human ,“p ní ọdún 2003..
wikipedia
yo
Rotimi kó ipa ribiribi nínú ìṣẹ̀dá Human Herredity and Health in Africa (H3Africa) pẹ̀lú ìrànwọ́ níh àti WellCome trust..
wikipedia
yo
Wọ́n yan án sínú ẹgbẹ́ National Academy of Medicine ni ọdún 2018.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Professor Olawale Sulaiman, MD.,PhD., FRCS(C), CON jẹ́ oníabẹtopọ̀ TO gbá Èkó ní Canada àti America..
wikipedia
yo
Ó sì tún jẹ́ onímọ̀ àti oníṣègùn àgbà ní Nigerian Heritage..
wikipedia
yo
Oun si ni oludari agba ni rnz global Ltd, eyi ti won ṣẹda ni odun 2010..
wikipedia
yo
ní ọdún 2019, wọ́n yàn án sípò Olùdámọ̀ràn fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara, lórí ọ̀rọ̀ ìlera.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Segun Toyin Daru (ti wọ́n bi ni ọjọ́ 13 Oṣù October, Ọdún 1960) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríàto si jẹ́ Oníṣègùn àrùn-ọpọlọ àti Agbẹjọ́rò pẹ̀lú Wellspan Health..
wikipedia
yo
O sise bi i ojogbon pelu Albany Medical College.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Dagogo-Jack jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó sì tún tan mọ́ ìlú American..
wikipedia
yo
Obioma Paul iwuanyànwu (ti won bi ni odun 1962) ti oruko re ni kukuru si je obiwu, je omo orile-ede Naijiria to tan mo ilu America..
wikipedia
yo
O je oluko agba ni Central State University.Afohun itọkasi..
wikipedia
yo
Wendy ONyinye Osẹ̀ (tí wọ́n bí ní May 21, 1984) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tàn mọ́ ìlú America..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ sí ètò òṣèlú, àti gbájúmọ́ orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní Johns Hopkins School of education..
wikipedia
yo
O ṣàfihàn nínu fíìmù àgbéléwò the Real Housewives of Potomac.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Kalu Nkakan Kalu jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ oníṣẹ́ tó n rí sí ọ̀rọ̀ òṣèlú..
wikipedia
yo
O si tun je ojogbon to n ko Political Science ati National Security Policy ní Auburn University Montgomery, ati ojogbon ní University of Tampere, Finlandàwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Saheed Aderinto (tí wọ́n bí ní January 22, 1979) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó n kọ History and African and African diaspora Studies ní Florida International University..
wikipedia
yo
Bakan naa lo jẹ onkọwe to ti gba ọpọlọpọ ami-eye..
wikipedia
yo
Ní oṣù February, ọdún 2023, Aderinto gba ẹ̀bùn $300,000, èyí tó jẹ́ ti dán David Prize..
wikipedia
yo
O ti ṣatẹ̀jáde iwe mẹjọ, Jona mẹrindinlogoji, àtikú ogoji ati Irilọ́gán sí Ìwé Ogun.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mazi elechukwu ńnàdíyípo Nnjaka (23 June 1921 – 14 January 1975) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà, àti onímọ̀ ọ̀rọ̀ òṣèlú..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún ìwé rẹ̀ Igbo Political Culture.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Olú Okeéko (tí wọ́n bí ní14 October 1964) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tàn mọ́ ìlú America..
wikipedia
yo
O jẹ ojogbon ni University of Connecticut, Storrs, o si tun je omo-egbe agba ni Vera list center for art and politics, ni New York City, ati Smithsonian Institution ni Washington, DC.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Nkechi MaDonna adeléine múrad (tí wọ́n bí ní October 8, 1962) jẹ́ olùkọ́ ẹ̀kọ́ ìṣirò ní irúfẹ́ of Manhattan Community College, èyí tó jẹ́ apá kan ti City University of New York.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
àbbá Gumel jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó ń kọ́ ẹ̀kọ́ ìṣirò ní University of Maryland, College Park..
wikipedia
yo
Gumel fìgbà kan kọ Ìṣirò ní Arizona State University, kí ó tó di alága The Michael and EUe brin Ajete E-Nnnate, ní University of Maryland, College Park, ní ọdún 2022.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Benjamin Ola Akande jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó sì tún jẹ́ onímọ̀, ọ̀jọ̀gbọ́n àti oníṣòwò ńlá..
wikipedia
yo
Ní oṣù May, ọdún 2021, wọ́n fi sípò igbá-kejì Ààrẹ, Director Human Resources, Head of Diversity and Faléọn, stiel Financial, èyí tó jẹ́ Ilé-iṣẹ́ ìfowópamọ́ tó ń rí sí ìdókòwò..
wikipedia
yo
Oun ni Aare kokanlelogun ti Westminster College ni Fulton, Missouri.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Joseph Abiodun Balogun, , (ti wọ́n bi ní January 1, 1955) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ onímọ̀, àti ọ̀jọ̀gbọ́n ní College of Health Sciences ní Chicago State University, Illinois àti University of Medical Sciences, ní ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O wa nipo diini College of Health Sciences ni Chicago State University © lati ọdún 1999 wo 2013..
wikipedia
yo
Lásìkò tó wà ní ipò yìí, ó ṣiṣẹ́ ìwádìí lórí àrùn HIV/AIDS.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Akingo jẹ́ olórí-ẹ̀kọ́-gíga Kejìlá ti North Carolina Central University..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn án sípò yìí ní ọjọ́ 26 osù June, ọdún 2017.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Okwui Enwezor (23 October 1963 – 15 March 2019) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó jẹ́ olùtọ́jú Muṣiọ́, Áṣárì, Akon sí Ìṣe-ọ̀nà, òǹkọ̀wé, akéwì àti onímọ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, wọ́n tó o pol mọ́ ojú-un àwọn ènìyàn tó ń ṣiṣẹ́ ọnà.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ọpẹ́rin sọ́tọ̀nwá (ti wọ́n bí ní Ìjẹ̀bú-Òde) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America..
wikipedia
yo
Arákùnrin yìí jẹ́ agbẹjọ́rò fún àwọn odi, ajàfẹ́tọ̀ọ́ àwọn odi àti òǹkọ̀wé ìwé lítíréṣọ̀..
wikipedia
yo
Ni Oṣu February, ọdun 2021, Gomina Charles Baker yan an sípò Komisona ati Olori Massachusetts Commission fún àwọn Odi..
wikipedia
yo
Kí wọ́n tó yàn án sípò yìí, ó jẹ́ adarí àgbà fún Missouri Commission fún àwọn odi.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ayọ̀ tómétò (tí wọ́n bí ní August 15, 1984), tó fìgbà kan jẹ́ Oòl Toigta, jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn, ònKól,wẹ̀, àti olùṣètò ìlú..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Olùṣẹ̀dásílẹ̀ Black Lives matter (BMB)..
wikipedia
yo
Ó sì fìgbà kan jẹ́ olùdarí agbá Black Alliance for just imMigration (Baji), níbi tó ti ṣiṣẹ́ fún Oṣù mẹsan-an.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Agwunobi jẹ́ ọmọ Scotland, tó sì tún tan mọ́ orílẹ̀l-èdè Nàìjíríà, tó jẹ́ oníṣègùn àwọn ọmọdé, ó sì fìgbà kan jẹ́ adarí àgbà àti alága Herbálì Nutrition..
wikipedia
yo
Oun si ni Igbakeji Aare ti WalMart, ati Aare Retated Health and Wellness Business lati ọdun 2007 wo 2014.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Tayo casalOṣù jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ oníṣòwò, tó tún ṣẹ̀dásílẹ̀ Págà, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó fàyè gba sísan owó láti orí ẹ̀ro-alágbèéká wa..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Págà kọ́kọ́ gbòde.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Adebayo Alonge jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ olóògùn àti oníṣòwò..
wikipedia
yo
Oun lo jawe olubori fun idije ti odun 2019 ti Hello tomorrow Global Dptech Challenge, eyi ti awon eniyan mo si bùkún Paribas Group deep Tech Award..
wikipedia
yo
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ yìí látàrí irinṣẹ́ kan tó lè ṣàwárí oògùn èbù tí ó ṣẹ̀dà..
wikipedia
yo
O jẹ okan lara awon Olùṣẹ̀dásile RxAll INC.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Tiffany ariana Trump (tí wọ́n bí ni October 13, 1993) jẹ́ ọmọ kẹrin ti àárẹ̀ U.S ìgbà kan, èyí tí í ṣe Donald Trump..
wikipedia
yo
Tiffany sì ní ọmọ kan ṣoṣo ti ìyàwó kejì Donald B.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Patrick Joseph Wilson (ti a bi ni ojo keta osu keje odun 1973) je osere omo orile ede Amerika..
wikipedia
yo
O bẹrẹ iṣẹ rẹ gege bi oṣere ni ọdun 1995, nigba ti o ṣere ninu Broadway Musicals..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn mọ́ ara àwọn tí ó tò sí Tony Awards ní Jordani fún ipa nínú eré The full Monty (2000-2001) àti Oklahoma! (2002)..
wikipedia
yo
O tun ṣere ninu ere Hbo ti akole re je Angels in America (2003), eyi ti o mu ki won yan le meji mo ara awon ti o to si ami eye Golden Globe Award ati Primetime Emmy Award.Wilson farahan ninu awon ere bi the IpààlàTom of the opera (2004), Hard Candy (2005), Little Children (2006), watchmen (2009), ati the a-team (2010)..
wikipedia
yo
O gbajumọ si nigba ti o farahan ninu ere Indious Film (2010-2023) ati gege bi ed Warren ninu ere The Conjuring Universe (2013-titi di ìsinsìnyí)..
wikipedia
yo
Ken Watanabe (Du Bian QIan , tí a bí ní Ọjọ́ kanlelogun Oṣù Kẹwa Ọdún 1959) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Japan..
wikipedia
yo
O gbajumọ laarin awọn elédè Gẹẹsi fun ipa rẹ gẹgẹ bi General Tadamichi Kurìbáyashi ninu ere Letters from iwo Dma ati gege bi Lord Andrewmoto Morimatsugu ninu ere The Last Samurai, eyi ti o mu ki won yan kun awon ti o to si Academy Award for Best Supporting Actor..
wikipedia
yo
Awon ami eye miran ti o ti gba ni Japan Academy Film Prize for Best Actor léméjì, akoko ni ọdun 2007 fun Jehovahes of tomorrow ati ekeji ni odun 2010 fun Shizumanu Taiyọ..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2022, o ṣere ninu ere Hbo Max ti akọle rẹ jẹ Tokyo Vice...
wikipedia
yo
OgunLesi CON (ti a bi ni December 20, 1953) je agbejoro ati oni-idokowo ọmọ orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Òun ni olùdarí àgbà fún Global Infrastructure Partners (gi)..)..
wikipedia
yo
OgunLesi fìgbà kan je olori won ni credit Suisse first Boston ki won to yan an sipo Alaga.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Maya Horgan Sodara jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ oníṣòwò, àti olùdásílẹ̀ Ingressive..
wikipedia
yo
O ṣẹdasile ile-iṣẹ kan ti orukọ rẹ n jẹ High growth Africa Summit, ati Tech Meets entertainment Summit..
wikipedia
yo
Maya pelu awon elegbe re (Sean burrowes ati Blessing Aabe) tun se idasile ingressive for Good.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Magnus lekara Kpákól ni adarí àgbà àti alága fún Economic and Business Strategies, ìyẹn Ilé-iṣẹ́ tó ní ẹ̀ka iṣẹ́ ní ìlú òyìnbó àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olùdarí agba àti akọrunlẹ̀ ní Economic and Business Strategies Ltd..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2001, Ààrẹ Olusegun Obasanjo yàn án sípò olùdámọ̀ràn fún ọrọ̀ ajé.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Angélica Nwandu (tí wọ́n bí ní May 10, 1990) ni olùdásílẹ̀ the Shade room (tsr), èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayélujára tó níṣẹ́ pẹ̀lú ṣíṣe òfófó àwọn gbajúmọ̀..
wikipedia
yo
Iye àwọn ènìyàn tó ń wo ètò yìí ń lọ bí i 20 million..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016,The New York Times to the Shade Room sábẹ́ àwọn ètò tó gbajúmọ̀l jù lọ ní orí ẹ̀rọ-ayélujára.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Adeyinka Fale (tí wọ́n bí ní June 20, 1976) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tàn mọ́ ìlú America, tó jẹ́ olùṣèlù àti ológun fún ìlú America..
wikipedia
yo
O gboye Bachelor of Science lati United States Military Academy ni West Point ati Juris Doctor lati Washington University in St..
wikipedia
yo
Adéoyè "Oyè" Owólẹwà (tí wọ́n bí ní ọdún 1989) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ olóṣèlú, olóògùn, àti ọmọ-ẹgbẹ́ Democratic Party..
wikipedia
yo
Ní Oṣù November, Ọdún 2020, wọ́n yàn án sípò ilé Ìgbìmọ̀ aṣofin ti orílẹ̀-èdè America.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo