cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ueto Young Agbaji (ti a bi ni April 20, 2000) je agbaboolu alapere fun Utah Jazz eyi to je ti National Basketball Association (NBA)..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí i ọ̀gá àgbà ní University of Kansas, wọ́n fún àgbàjí lórúkọ, wọ́n sì dìbò fún ní ọdún 2022, gẹ́gẹ́ bí i Big 12 Player of the Year..
wikipedia
yo
O dari ẹgbẹ Jayks ninu idije, titi won fi wo ipele to keyin, won si so won ni Final four most ologóṣẹ player (mop).Awon itọkasi..
wikipedia
yo
(tí a bí ní October 19, 1989) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America..
wikipedia
yo
O jẹ agbabọọlu àlájùṣàpẹrẹ, to gba bọọlu fun Maccàbí Tel Aviv, eyi ti i ṣe ti Israẹli Basketball Premier League ati EuroLeague..
wikipedia
yo
O tun gbacasallu fun ile-iwe giga ti Rice University, ki o to bẹrẹ Sim maa gba bọọlu fun NBA development League, ni Qatar, Japan, New Zealand, Mexico, Germany, Russia, France, Israel, ati Turkey.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Chamberlain "Champ" ReEmeka Oguchi (ti a bi ni April 28, 1986) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àlájùsàpẹrẹ, tó gbá bọ́ọ̀lù náà fún Boula;” Basket Dormasne, ti Utue Pro B..
wikipedia
yo
Oruko re "Emeka" je agékúrú orúkọ Igbo rẹ̀, tí ń ṣe "£Emeka", (ti ìtumọ̀ rẹ̀ jẹ́ "Ọlọrun ti ṣeun púpọ"). pọ̀..
wikipedia
yo
John Malkovich (tí a bí ní ọjọ́ kẹsan oṣù kejila ọdún 1953) jẹ́ oṣere ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹrika..
wikipedia
yo
O ti gba ọpọlọpọ ami-eye, awọn bi Primetime Emmy Award, won si ti yan mo awon ti o to si ami-eye Academy Awards léméjì, BAFTA Award, screen Actors Guild Awards, ati ami eye Golden Globe Awards lémẹ́ta.Malkovich bẹrẹ iṣẹ osere gege bi nigba ti o darapọ mo egbe steppenWolf Theatre company ni Chicago ni ọdun 1976..
wikipedia
yo
Àwọn fíìmù tí ó ti ṣeré ní True West (1980), Death of a salesman (1984), the Caretaker (1986), àti ní burn This (1987), Places in the heart (1984), in the Line of fire (1993), The killing Fields (1984), Empire of the Sun (1987), Dangerous dúńbúSons (1988), of mice and Men (1992), Con Air (1997), rounders (1998), Being John Malkovich (1999), Shadow of the Vamire (2000), Ripley's Game (2002), burn After Reading (2008), and Red (2010)..
wikipedia
yo
O ti ṣe agbejade awọn fiimu bi Ghost World (2001), Juno (2007), ati The Lober of Being A Wallflower (2012).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mark Richard HaMill (; ti a bi ni ọjọ karundinlogbon oṣu Kẹsán-an ọdun 1951) jẹ oṣere ọmọ orile ede Amẹrika ati Olukọwe..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Luke SkyWalker nínu àwọn eré Star Wars..
wikipedia
yo
O bẹrẹ ni original 1977 Film wọn si fun ni ami eye Saturn mẹta fun ipa rẹ ninu The Empire strikes back (1980), return of the dìdí (1983), ati The Last Jedi (2017)..
wikipedia
yo
O ṣere ninu awọn ere miran bi Coragbéraga Summer (1978) ati the Big Red One (1980)..
wikipedia
yo
Harrison Ford (tí a bí ní Ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Keje Ọdún 1942) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O ti farahan ninu ọpọlọpọ ere, opo si mo si cultural icon orile ede Amerika..
wikipedia
yo
Àwọn eré tí ó ti ṣeré ti pa tó iye owó tí ó lé ní bílíọ̀nù márùn-ún dọ́là ní Àríwá Amẹ́ríkà àti iye tí ó lé ní bílíọ̀nù mẹ́sàn dọ́là káàkiri àgbáyé, ó ti gba ọ̀pọ̀ àmì-ẹ̀yẹ bí àfi Life Achievement Award ní ọdún 2000, Cecil B..
wikipedia
yo
Demille Award ní ọdún 2002, Honorary César ní ọdún 2010, àti Honorary Palme' B'Or 2023, Wọ́n sì ti yàn rí mọ́ mọ́ àwọn tí ó tọ́ sí àmì ẹ̀yẹ Academy.Díẹ̀ nínú àwọn eré tí ó ti ṣeré ní American Graffiti (1973), The conversation (1974), Star Wars (1977), Riders of the lost Ark (1981), Blade Runner (1982) àti Blade Runner 2049 (2017), Patrio Games (1992), clear and Present Danger (1994).Wọn Yan Ford mọ́ Ara àwọn tí ó tọ́ sí àmì ẹ̀yẹ Academy Award for Best Actor fún ipa rẹ̀ nínú eré Witness (1985).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Anthony Daniels ( ; tí a bí ní Ọjọ́ kanlelogun Oṣù Kejì Ọdún 1946) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain, tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ fún ipa gẹ́gẹ́ bi nínu eré Star Wars mẹ́wàá..
wikipedia
yo
Daniels ni ó fọ́ Ohùn fún Legolas nínu eré Ralph bakshi bèbí tí wọ́n ṣe fún The Lord of the rings (1978)..
wikipedia
yo
Daniels jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n ní Entertainment Technology Center ti Yunifásítì Carnegie Mellon.Ìpilẹ̀ rẹwọn bi Daniels ní ìlú Salisbury, Wilya, England..
wikipedia
yo
O kawe ni ile iwe gíglesles school o si kẹkọọ nipa imo ofin fun ọdun meji ni Yunifasiti, ṣugbọn o kuro lati kopa ninu Amateur Dramatics leyin ti o pada lo Rose Bruford College..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó kàwé gboyè ní Burford College ní ọdún 1974, Daniels ṣiṣẹ́ ní on BBC Radio àti fún Gbọ̀ngàn Eré National Theatre ti Great Britain ní The Young Gvic..
wikipedia
yo
Nibi ti o ti n sise ni gbongan naa ni won ti pe lati pade George Lucas, eni ti o n wa awon eniyan lati sere ninu Star wars.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Crystal Clarke (ti a bi ni ọdun 1993 tabi ọdun 1994) jẹ oṣere ọmọ orile ede Amẹrika..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ mọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Tina Argyll nínu eré BBC àti Amazon Prime tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Ordeal by Innocence (2018) àti gẹ́gẹ́ bi Georgiana Lambe nínu eré ITV àti Pbs tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Kánádàton (2019-ìpílẹ̀wọn bí Clarke ní EsSex County, New Jersey, sínú ìdílé àwọn òbí Caribbean; wọ́n tọ́ dàgbà nínu ìlú kan náà náà; ìyá rẹ̀ wá láti Trinidad, bàbá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Guyana..
wikipedia
yo
Clarke lo ile iwe Newark arts high school, o si kẹkọọ gboye ni odun 2011.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Billie Catherine K€d (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún Oṣù Keje Ọdún 1992) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi L Chanel #3 nínu eré Fox tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Sewed Queens (2015–2016) àti ipa rẹ̀ nínu Fx tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ American Horror Story (2017-títí di ìsinsìnyí)..
wikipedia
yo
Ó farahan gẹ́gẹ́ bi Lieutenant Conìpèṣo nínu àwọn eré Star Wars Sequel (2015–2019)..
wikipedia
yo
Lourd nikan ni omo òṣèrébìnrin Invel Fisher.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Judah Friedlander (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógun oṣù kẹta ọdún 1969) jẹ́ òṣèré àti aláwàdà ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi akọ̀wé Frank Rossider nínu NBC sitcom 30 Rock..
wikipedia
yo
Friedlander tún gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Toby Radloff nínu eré American Splendor, ipa tí ó mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ gbóríyìn fún, ó sì mú kí ó wà lára àwọn tí wọ́n yàn pé ó tọ́ sí àmì ẹ̀yẹ 2004 Independent Spirit ti ọdún 2004..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, ọ̀pọ̀ ma n pè é ní "The Hug Guy" nítorí ipa rẹ̀ nínu eré tí Dave Matthews band ṣe fún orin rẹ̀ "Everyday". * Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Thomas Brodie-Sandington (tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù Karùn-ún Ọdún 1990) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain..
wikipedia
yo
O gbajumọ fun ipa rẹ gẹgẹ bi Sam Love actually (2003), Simon ninu NANNY McPhn (2005), Ferb ninu Phineas and Ferb (2007–2015), JoJẹ́n Reed ninu game of Thrones (2013-2014), Newt ninu Maze Runner Film (2014-2018), ati Benny Watts ninu ere Netflix ti akori rẹ jẹ the Queen's Gambit (2020), eyi ti o si mu ki won yan mọ ara awon ti o to si ami eye Primetime Emmy Award.How- tun tun gbajumọ si nigba ti o ṣere ninu awọn ere bi Death of a Superhero (2011), Bright Star (2009), ati gẹgẹ bi Paul McCartney ninu nowh Boy (2009–
wikipedia
yo
Ìlàjẹ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní ìpínlẹ̀ Oǹdó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ẹ̀yà Yorùbá yìí dá yàtọ̀, nínú èdè ẹnu wọn, àkójọpọ̀ ìlú bí i Òǹdó, ogun àti Delta ló bí ìlú yìí.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ada je okan lara awon ilu to wa ni agbegbe ijoba ibile boripe, ni IpinleOsun, ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oba Oyetunde Oluwatun Ojo (The ọlọ́nà of Ada) ni olori ilu naa.Lára àọn lo wa ni ilu naa ni ile oba oludélé oludélé, ile Adeitan, ile oba Olugbogbo ile aro, ile Alágbaà, Ojomu Owayeola, Oalade, Eode, jagun, Osolo, Oke Baale, Asasile, Oluode, Agba Akin, ati Ile Odògun.Àwọn itọkasigun..Àwọn
wikipedia
yo
Gilbert Bani (ti wọ́n bi ní August 1, 1986), ti orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ si jẹ́ A-Q, jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti akọrinsílé.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Abrams, ẹni tí ó jẹ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀ darí bí àpẹẹrẹ, Felicity nínú Sean Bluberg..
wikipedia
yo
O tun ṣere ninu ere Showtime ti akole re je Masters of Sex.Ìpìlẹ̀ re a bi grunberg ni ilu Los Angeles, California, sinu idile Sandy (née Klein) ati Gerry grunberg won si to dagba ni ilana Juu..
wikipedia
yo
Ó lọ ilé-ìwé University High School ní West Los Angeles.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Leslie Schfield (tí a bí ní Ọjọ́ kejìlá Oṣù kejìlá Ọdún 1938) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain tí ó gbajúmọ̀ ní United Kingdom fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Jeff Healy nínu Soap opera Eastenders, ó kó ipa yìí láàrin ọdún 1997 sí 2000..
wikipedia
yo
Awon ere miran ti o ti farahan ni the body Stealers (1969), Twinsky (1969), Villain (1971), the Ruling Class (1972), The Gliterball (1977), The Wild Gese (1978), Force 10 From Nakúnnene (1978), Silver Dream Racer (1980), Dead Man's gbígbẹ́ (1986), Doctor Who, The War Games (1969) The Face of Evil (197ati, Bee bẹẹ lọ..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ àwọn eré tí ó ti kópa ni Batman, Spy Game, Me and Orson Welles àti The Message..
wikipedia
yo
Òun ni ó kópa àgbà nínú eré The Mutants, ó sì kópa Simon Gerrard, ọkọ Debbie Aled- ninu eré tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ The Káas.Ìpilẹ̀ àti iṣẹ́ rẹ̀wọ́n bí Ggon ní London, England, wọ́n sì tọ́ dàgbà ní Toronto, Ontario, Canada, níbi tí ó ti lo ilé ìwé fọ́nOlùràpadà àti Trinity College (Hon..
wikipedia
yo
Ó ṣeré pẹ̀lú Alec Guinness nínu eréRichard III ní Stratford Festival, èyí tí ó mú kí ó gba àmì-ẹ̀yẹ Tyrone GUminrie Award ní ọdún 1963.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
pernilla August (; orúkọ tí àwọn òbí rẹ̀ fún ní Mia pernilla Hertzman-ICson; tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Kejì ọdún 1958) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè SWEDEN..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèrébìnrin tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní Sweden, ó sì ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ pẹ̀lú Somar Bergman, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Best Actress ní ayẹyẹ Cannes Film ti ọdún 1992 fún ipa rẹ̀ nínu The Best Intentions..
wikipedia
yo
fún eré kan náà, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Best Actress ní 28th Guldkoge Awards.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
gurdeep Roy (oruko ibi re ni Mohinder purba; ti a bi ni ojo kinni osu kejila odun 1957), ti ọpọlọpọ mo si deep Roy, jẹ oṣere ọmọ orile ede Kenya ati Britain..
wikipedia
yo
Nitori pe ko ga tara(giga rẹ ko ju lọ, o ma n saba kopa awọn eniyan ti ko ga ninu awọn ere, bi apẹẹrẹ gege bi Teeny Kukuy ninu The Neverending story ati óoRadio-fistedness ninu Charlie and the chocolate factory, keenser in Star Trek, ati ninu awon ere bi The x-Files, Doctor Who, ati Eastbound & Down.Nípa ayé ati ise rẹwọn bi Roy ni ojo kinni osu kejila odun 1957 nínáìrọbí sinu idile India(awọn obi rẹ je ọmọ orile-ede India)..
wikipedia
yo
Ó lo ilé-ìwé láti kọ nípa ìṣirò ní London kí ó tó fi ilé ìwé sílẹ̀ nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún méjìdínlógún..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré pẹrẹwu ní ọdún 1976 nínu ìsọ̀rí kẹrìndínlọ́gọ́rin eré The New avengers, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Target, ó kópa gẹ́gẹ́ bi Klọkọe..
wikipedia
yo
O ṣere ni ọdun kan naa ninu ere The pink Panther strikes Again..
wikipedia
yo
Emeka akumelọ́rọ̀, ti oruko inagijẹ re n je Blaqboramúramù, je olorin orile-ede Naijiria.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Oladipo Olamide Emmanuel (ti won bi ni 13 September 1993), ti oruko inagijẹ re si je Chinko ẹkùn, je olorin ati akorin sile orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
O kẹkọọ gboye latiObafemi Awolowo University.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
FFF Mobolaji Gaius, tí orúkọ eré rẹ̀ ń jẹ́ Da Emperor, jẹ́ olórin, òṣèrékùnrin àti akọrinsílẹ̀ tó wá láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Haruna Abdullahi (tí wọ́n bí ní 30 December 1993), tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ DJ Ab, jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Tìṣòrochukwu Yẹful tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ illBliss, jẹ olorin ati onisowo ti orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun si tun ni adari agba fun ile-iṣẹ 'The Gikutti company'.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Ian Frederick Oshodi (tí wọ́n bí ní 30 March 1986), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sí ń jẹ́ Ian Jawyndila, jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Ghana, Totan mọ́ Nàìjíríà, jẹ́ ọlọ́rin, òṣèrékùnrin àti oníṣòwò.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ládípọ̀ èso ti orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ n jẹ́ Ládípọ̀e tàbí pòẹ̀ jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríàani 28 February 2017, Ládípọ̀e tẹ́wọ́bọ̀wé láti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́-olórin Mavin Records.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Jesse James Enoch (tí wọ́n bí ní 14 September 1983), tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ jẹ́ Lyrikal, jẹ́ olórin orílẹ̀-ede Nàìjíríà, àgbọ̀rínjáde àti akọrinsílẹ̀.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Babatunde Olusegun Adewale(ti won bi ni June 14, 1975), ti oruko inagijẹ re n je Modeni, je olorin..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ó ṣàgbéjáde orin kan, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Super Human" pẹ̀lú akọrin ti orílẹ̀-èdè Jamaica kan, tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ AniBus.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
aniBus je oruko inagijẹ fun Germaine Williams (ti won bi ni December 9, 1974) je olorinàwọn itọkasi..
wikipedia
yo
A A-Q Eedris Abdulka Eva alodiahb Andre Blaze BlaqbotìLatvia Base Onec CDq Chinko ẹkùnd Da Emperor da Grin (deceased) d'Ban Dr Sid dúrélla DJ Ab dice Alèṣe eldee Emmy Satun EriCompare Efef Guzi Ice Prince ill illry Ikechukwu Ikechukwu Jesse Kógg Jòhel JÒH JaÀyà Anatyl jẹri AravEE Z Ladipoe Lay Con K KSHv الR M.I Àbá M- 2016- Mo Mo' Mode 9 N eto co Fi Oduvv V * Prace Mi Rece Miny Rẹ̀ ] Skales Sasha p V Rictor W' Wrd Mcy y Y' Y' S S' FM S[2] A * FM E 2016 E Mo FM Mo O O Re' D _* 2 Ece 2020 A Lil O ce I 2017 2016 - Ece *BO FM N Mọ́mì * Chin *Of [ N Kan Mo M A Women E ce * 2017 FM Ece A 2017 & E Mo 2017 Mo 2017 _*E N 2017 N Kan 2017 A FM O S E O Se B V S S Kan O N 2017 Mo E * FM FM S Mo 2016 E N A _ * & * * D 2016 Mo 2016 ****
wikipedia
yo
Tochukwu gbúbémi Ojogwu (ti won bi ni 18 October 1993), ti oruko inagijẹ re je Odudepobvck je olorin orile-ede Naijiria.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Gowọle Gbenga Kayode (tíwọ́n bi ni 16 April 1988), ti Oru,ko inagijẹ re si je pẹpẹnazi, je olorin Takasúfèé ti orile-ede Naijiria.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Chibuzo Nelson Azubuike (tí wọ́n bí ní 9 October 1986), tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ jẹ́ Phyno, jẹ́ olórin, Olórin Takasúfèé àti àgbọ̀rínjáde ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Phy ti kọrin pẹlu awọn olorin bi i Olamide, Wizkid, Davido, tiMaya, flaour, Ruggedman, Bracket, J..
wikipedia
yo
Chinedu okoli (ti won bi ni 23 November 1983), ti oruko inagijẹ re n je flaour n'abania tabi flavour, je olorin orile-ede Naijiria.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ibrahim Mímọ̀d (tí ó kú tíṣe Oṣù-an Oṣù kejìlá ọdún 2009) jẹ́ onímọ àkàn (Sociologist), ònkọ̀wé àti òṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè ní ètò-òfẹsẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kejì Nigeria..
wikipedia
yo
Bákan náà, ó jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ẹgbẹ́ alákatakítí Kaduna Mafia..
wikipedia
yo
Kí o tó darạ̀ mọ́ Òṣèlú, ó jẹ́ onímọ àkàn tí ó gbajúmọ̀ nínú oyè Tramption Conservina.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Michael Ugochukwu Stephens, tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ruggedman, jẹ́ olorin Takasúfèé ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó wá láti Ohafia, Ìpínlẹ̀ Ábíá.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Bracket jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàíjíríà méjì kan, tí wọ́n ń kọ orin Afrọ́pò àti R&B..
wikipedia
yo
Orko awon olorin mejeeji yii je òbumneme Ali "Sikush" ati Nwachukwu Oziokova".àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Àjájá Àgéfúnfún, tí orúkọ ìgégégé rẹ̀ ń jẹ́ Vector, jẹ́ olórin Taka- orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
OluDemilade Martin Àlejò (tí wọ́n bí ní 29 January 1993), tí oruko ìnagijẹ rè sí n jẹ́ Ycee, jẹ́ olorin Takasúfèé ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Kaduna Mafia (kì í ṣe ẹgbẹ́ ọ̀daràn) bí kò ṣe ẹgbẹ́ àwọn olókòwò, òṣìṣẹ́ ìjọba, àwọn onímọ̀ àti àwọn ológun láti ìhà àríwá Nigeria tí wọ́n ń gbé ní Kaduna tàbí tí wọ́n ń ṣòwò ní Kaduna, tí ó jẹ́ olú-ìlú agbègbè apá àríwá nígbà náà ní ìparí sáà ètò ìṣèlú ẹlẹ́ẹ̀SI.Ẹgbẹ́ náà fara jo sícilian Mafia, ẹgbẹ́ tí oun náà fi iṣẹ́ jọ ẹ̀yà Omerta, Ethnicity..
wikipedia
yo
Wọ́n gbàgbọ́ pé àtakò ni o ṣokùnfà dídá ẹgbẹ́ náà sílẹ̀ tí wọ́n sì wa di ìlú-mọ̀ọ́ká àti gbajúmọ̀ tí wọ́n lágbára láwùjọ nítorí ìbáṣepọ̀ tí wọ́n ní pẹ̀lú àwọn aláṣẹ òṣèlú, tí wọ́n gbé agbára ìlú ka àwọn oníṣòwò àdáni, Cavbẹ̀rùsm.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ado Isah Gwanja (ti wọn bi ni 22 January 1990) jẹ olorin ti orilẹ-ede Naijiria, ati òṣèrékùnrin ninu àwọn fíìmù àgbéléwò ti apá Gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Oguntade Adewale Dje (ti won bi ni 27 June 1989), ti oruko inagijẹ re n je Ajimovo Drums, je olorin orile-ede Naijiria, Agborin, ati elere irinṣẹ́ irinrin lóríṣiríṣi.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ali Isah Julia (tí wọ́n bí ní 15 July 1983), tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ali Julia, jẹ́ olórin Hausa, ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Oyinkansola Sarah Aderibigbé (ti won bi ni 14 June 2002), ti oruko inagijẹ re si n je Ayra Starr, je omo orile-ede Naijiria ti won bi ni orile-ede Benin..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olórin tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ nípa ṣíṣe àkọ́túnkọ́ àwọn orin olórin lórí ẹ̀rọ-ayélujára, kí ó ṣe àgbéjáde orin tirẹ̀ gan-an gan..
wikipedia
yo
Orin rẹ̀ yìí ló pe àakiyesi Don Jazzy, tó mú wo ẹgbẹ́ orin tire tó ń jẹ́ Mavin Records.Awon ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Aoba Victor tí wọ́n bí ní 14 March 1999), tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ Babyboy Av, jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó wá láti ìdílé olórin kan tí wọ́n ń pè ní ‘The Aani's'àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Oyin1979 Johnson Emmanuel,ti oruko inagijẹ re n je dammy Krane, je olorin orile-ede Naijiria, ati elere.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Derek Osonwa, ti oruko inagijẹ re n jekum-Carkumgba, je olorin orile-ede Naijiria, atẹ dùrù ati akorinsile..
wikipedia
yo
O ti sise pelu awon olorin bi i Mr raw, flaour, Bracket, Dr Hanani, Charly Boy ati bee bee lo.Awon Iọkàsi..
wikipedia
yo
Áhábùh Uzoma Nwapa (tí wọ́n bí ní 26 August 1957), tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Dr..
wikipedia
yo