cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
30“ Wa sinu ayé ati pe a ti jíròrò ní kíkún ṣáájú kí o tó gbejade ni ìwé ìròyìn òṣìṣẹ́ ti 20 May 1921.O jẹ́ "Senate Orílẹ̀-èdè Olómìnira Kẹta" tí o ti jiyán lórí ẹ̀bẹ yìí lábẹ́ Ààrẹ Leon Bourgékù.lórúkọji ìjápọ àwọn ará Algeria..
wikipedia
yo
Estrotorí tàbí Otálákà jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn Homonu ìbálòpọ̀ tí tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ìdàgbà-sókè àti ìfètò sí ẹ̀yà ara ìbímọ lára àwọn obìnrin àti ìṣesí ìbálòpọ̀ lára obìnrin..
wikipedia
yo
ìpín mẹ́rin ni a lè pín estrogen sí látàrí ìṣesí àti iṣẹ́ wọn nínú ara obìnrin..
wikipedia
yo
EstradiOl, tí o tún ń jẹ́ Estranẹ, ni ó lágbára jùlọ tí ó sì wọ́pọ̀ jùlọ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Bákan náà ní estrogen tí wọ́n ń pè ní EsteOrí (Ẹ4) ni ó ma ń jáde nígbà tí obìnrin bá wà nínú oyún..
wikipedia
yo
Gbogbo ẹranko elégungun àti àwọn kòkòrò abìyẹ́ ni wọ́n ma ní estrogen lára..
wikipedia
yo
Tí a bá ní ká fòye mọ̀ọ́, lílọ bíbọ̀ estrogen nínú ara ọkùnrin àti obìnrin kìí fi bẹ́ẹ̀ pọ̀..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé estrogen kìí fi bẹ́ẹ̀ pọ̀ púpọ̀ lára ọkùnrin tó bí ó ṣe wà lára obìnrin, síbẹ̀, ó ní iṣẹ́ pàtàkì tí ó ń ṣe lára ọkùnrin.Gẹ́gẹ́ bí àwọn steroid hormone ti ń ṣiṣẹ́ ní estrogens náà rìn tàbí Paraji inú àgọ́ ara tí ó fi mọ́ inú àwọn sẹ́ẹ̀lì ara..
wikipedia
yo
Ní ké tí ​ estrogen bá ti wọ inú sẹ́ ara ni ó má ń rọ́pò tí ó sì má ń ji ohun tí wọ́n ń pè ní estrogen Recetor (ers) sílẹ̀ ní èyí òọ́ má ṣíṣe ààtò ìtaẹ̀dù àwọn jíjígbọ́n ara lọ́kan-ò-òkan ..
wikipedia
yo
Lori, estrogen tun ma n sise ijisile awon ohun ti won n pe ni membrane estrogen Recetors (mers), gege bi Gper (GPR8).Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Wọ́n sí musiọmu náà ní ọdún 1975 ní ìfítọrẹ fún ìlú ti àwọn Northern People's Congress (נפשׁ tẹ́lẹ̀) tẹ́lẹ̀ ti ijoba ipinle ti Àárín Gbùngbùn Ariwa..
wikipedia
yo
omuomu Kaduna naa kun fun akojọpọ awọn ohun pataki ti o ni ṣe pẹlu kíkọ́lé, ohun ìṣẹ̀ǹbáyé ati awọn oriṣiriṣi ohun iṣe ọna o si ni awọn ikanni iṣe ọna ti awọn oníṣẹ́-ọna lọkunrin ati lobinrin le maa wo lati kọ awọn iṣe-ọna naa.Awon itọkasis in NigeriaMuseum established in 1975Kaduna ..ments in Nigeria20th-Century Architecture in Nigeria..
wikipedia
yo
omuomu káńtà jẹ́ fúnni ní ìlú Argun, ní orílẹ̀ èdè Nigeria, tó dẹ̀gbẹ́ kọjú sí ọjà..
wikipedia
yo
wọn kóo ní ọdún 1831, wọ́n sì sọọ́ lórúkọ lẹ́yìn Muhammed káńtà, tí ó tẹ́ Kebbi Kingdom dó ní ọdún 1515..
wikipedia
yo
ti Yakubu nabame si kòo, ọba Kebbi, ti o si jẹ titi di 1942 ti àwọn aláwọ̀ funfun fi kọ́ ààfin tuntun ní àkókò ìjọba Muhammed Sani..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ààfin náà ṣófo, ní ọdún 1958, wọ́n síì gẹ́gẹ́ bíi musiọmu, tí ó ṣàlàyé àrànbá tí ó jẹ́ baba ìtàn ti ìpínlẹ̀ Kebbi.kìlómítà náà pín sí ìdá mọ́kànlá tí ó sì ní àwọn ohun ìrìnṣẹ́ ogun, tí ó kún fún ogun, ọ̀pọ̀ ìdàrọ́, ọ̀pọ̀ idà,igi, ọ̀pọ̀ òkúta, ọ̀pọ̀ ọfà àti òpó akọ, ìbọn àgbéléro àti bákan náà àwọn ìlú fún iṣafihan.Referencesnítorí in Nigeriabibi state-ó-sá-sá Architecture..
wikipedia
yo
òròn Museum jẹ́ ilé ti àwọn ohun ìṣèṣè lọ́jọ́ sí tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1958, tí ó wà ní ìlú òròn òrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ..
wikipedia
yo
Wọ́n dá ilẹ̀ ìṣèṣèṣè yí sílẹ̀ ní ọdún 1958 láti lè kọ́ àwọn ohun ìṣèṣèdínlógójì tí wọ́n tó di ọgọ́rùn mẹ́jọ, tí wọ́n ṣe pàtàkì sí àṣà àti iṣẹ́ àwọn ẹ̀yà òrò tí wọ́n gbà wípé wọ́n wà lára àwọn ẹ̀yà tí wọ́n ti pè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n sì jẹ́ ẹ̀yà tí wọ́n mọ iṣẹ́ gbẹ́nàgbẹ́nà ṣe jùlọ ní ilẹ̀ ilẹ̀ adúláwọ̀ lásìkò.Lásìkò kan kan, wọ́n ṣe ìkọ́lé sí ilẹ̀ ìṣèṣè náà tí wọ́n sì jí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn igi tí wọ́n ti ṣiṣẹ́ sí lára náà kó lọ, tí wọ́n sí ilẹ̀ ìṣèṣèdínlógójì ná jẹ́ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Ọdún 1975, ìjọba tún ilẹ̀ ìṣèṣè náà dìde padà tí wọ́n sì ṣe àwọn igi tí wọ́n ti ṣiṣẹ́ aláwábara sí lára tí wọ́n ṣẹ́kù àti àwọn míràn káàkiri orílè-èdè Nàìjíríà síbẹ̀..
wikipedia
yo
Lara awon igi ti won pata re sibe ni odi ti won fi dáàbò bo awon ohun ṣèdájọ́ naa lasiko ogun ati awon nkan miran to ku sinu ilu naa leyin ogun.Awon itọkasiòrò PeopleMuseum in NigeriaMuseum established in 1958Akwa Ibom State20th-Century Architecture in Nigeria..
wikipedia
yo
Ilé ṣèṣèṣè ìlú owó jẹ́ ilé Ìṣèdínlógójì ńlá kan tí ó wà ni ìlú ìlú òwò, ní ìpínlẹ̀ Òndó ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n dá ilẹ̀ wéréwéré náà sílẹ̀ ní ọdún 1968 láti lè kó àwọn ohun Schoolṣè ayé àtijọ́ tí kò sírú rẹ̀ mọ́ síbẹ̀..
wikipedia
yo
Inú àgbàlá ààfin olówó ni ilé ọ̀jẹ̀ṣè yí wà tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Ile iseṣèwe naa ni awon ohun mèremère ti won je ohun aye atijọ ninu.odun 9169 si 1971 ni won koko wa awon ohun iseṣèwe kan jade lati owo ekpo ke ninu ile ni ilu owo labe ase eka ijoba ti o n ri si ohun àlúmọ́nì Aye atijọ..
wikipedia
yo
Àwọn ohun tí wọ́n rí wa jáde nínú ilé náà ni Terracotta Ifènìyànres tí wọ́n ti lò tó ṣétúrì mẹ́ẹ̀ẹ́dógún sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Ìdíbni wípé, ìlú ọwọ́ jẹ́ ìlú tí ó wà ní àárín gbùngbùn ilé-Ifẹ̀ àti ilẹ̀ Ìbìní.Àwọn ìtọ́kasíMuseum in NigeriaMuseum established in 1968owo20th-Century Architecture in Nigeria..
wikipedia
yo
Ulli Ògúnjáde Museum jẹ́ ilé-iṣẹ́ aṣṣàfihàn àwòrán àti ilé-ìwé àwòrán ní Òṣogbo Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O jẹ idasilẹ nipasẹ awọn aṣawòrán Ulli polówó ati Susanne Wenger..
wikipedia
yo
Lónìí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ aṣṣàfihàn àwòrán Áfíríkà àsìkò tí ó ṣe pàtàkì, tí ń gbàlejò iṣẹ́ àwọn asawòrán tí ó ní òye àti àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń dàgbà sínú iṣẹ́ láti agbègbè Òṣogbo àti ní gbogbo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìtọ́kasís] in niáa art Museumṣoṣogbo Museums and Galleries in Nigeria..
wikipedia
yo
omuomu Èsìẹ́ jẹ́ musiọmu ní ilé Èsì, ní Ìpínlẹ̀ Kwara, ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
omuomu yìí jẹ́ alákọ́kọ́ tí wón kọ́kọ́ da sílẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nígbà tí wón síi ní ọdún 1945..
wikipedia
yo
omuomu yìí fẹ̀kan tẹ́lẹ̀ rí gba ọgọrun-un àwọn ère olókùúta ìtẹ́kú tí wọ́n fi dípò àwọn eniyan..
wikipedia
yo
Ìwúrí ni láti ní àtòpọ̀ àwọn àwòrán eré olókúta tí ó pọ̀jù lọ lágbàáyé..
wikipedia
yo
Láyé òde-òní musiọmu Èsìẹ́ ti di gbọ̀ngàn ètò ẹ̀sìn àti ibi tí wọ́n ti ń ṣe ayẹyẹ ní oṣù kẹrin gbogbo ọdún.Àwọn ìtọ́kasís in NigeriaMuseum established in 1945Kwara State20th-Century Architecture in NigeriaTourist forúkọctions in Kwara State..
wikipedia
yo
káńtà musiọmu wà ní argungu ní ìlú Nàìjíríà, tí ó kọ ojú sí gbàgede ojú ọjà gangan ní ọdún 1831 ní a kó káńtà ìjòyè, wọ́n fún ilé náà ní orúkọ lẹ́hìn Muhammed káńtà láti lè máa ṣe ìrántí fún - un, ọkùnrin yìí náà bákannáà ni ó dá ìjọba Kebbi sílẹ̀ ní ọdún 1515..
wikipedia
yo
Yakubu nabame, ni ó fi ilé náà lé lé, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Emir tí ó tí jẹ́ sẹ́yìn ní ọdún 1942 nígbàtí àwon Gẹ̀ẹ́sì kọ́ ilé-iṣẹ́ ìṣàkóso titun ní àkókò ìjọba Muhammed Sani ..
wikipedia
yo
Lẹhin ti ile naa ti wa ni ofo , ni osu keje, ojo kinni, odun 1958, won fi ile naa si musiọmu ti o fun ni ni oye awon itan rudurudu tabi iwa ipa ti o sele ni Ipinle Kebbíipínlẹ̀ Kebbi . naa pin si iyẹwu mokanla, o tun ni Ìkójọpọ̀ awon ohun ija, ti o ni awon awon oko, ida, igi, awon òkúta, ọfa , awon ibon ibile pelu awon ilu ti won fi se ifihan sinu ile naa .Awon itọkasi Ipinle Kebbi..
wikipedia
yo
Benin City National Museum jẹ́ musiọmu ní ìlú Benin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà , tí ó wà ní àárín ìlú King's Square..
wikipedia
yo
Sìǹbábúwè náà Ní àwọn ohun-ọ̀ṣọ́ tí ó ṣe pàtàkì sí ìjọba Benin bíi ìkọ̀kọ̀ amọ̀ tàbí àwọn àwòrán tí wọ́n fi amọ̀ ya [[Terracotta],,àti àwọn irin tí a ti jó pọ̀ ..
wikipedia
yo
O tun ni awọn aworan aworan atijọ ti o jẹmọ ìgbàanì the Benin City Museum wà ní agbègbè ibi kan ti wọn n pe ní ring ti àwọn ará ìlú ìlú Benin maa n pe ni King's square, ṣugbọn ti com tikedere Adams Oshisíbihole yí pada si Ọba Ovonn Square lasiko ti o wa ni ipo gomina ipinle naa.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Kíre] Kumar G ni a bini ojo kefa dinlogun, osu August ni odun 1974 je osere lọkunrin ti ile India ti a mo si Kaláriwo..
wikipedia
yo
Gidan Maka Museum Kano tàbí Kano Museum jẹ́ Setióo kan ní Ìpínlẹ̀ Kano, ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ yìí fìgbà kan jẹ́ ààfin tí Sarakunan Hausa (èyí tó jẹ́ Ọba àwọn Hausa) tí Kano, ṣááju Ààfin tó wà níkalẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́, ti Gidan Rumfa, ní Ajetúrì Kẹẹ̀ẹ́dógún..
wikipedia
yo
Muṣioo yìí ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn iṣẹ́-ọnà tó lààmìlaaka àti àwọn nǹkan tó wúlò fún ìtàn tí ó tan mọ́ Kano, àti agbègbè rẹ̀..
wikipedia
yo
Tí wọ́n ṣawari ní Sétúrì kẹẹ̀ẹ́dógún, tí wọ́n sì dá mọ̀ bí í ilẹ̀ ìranti ti ìjọba Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Muṣióo yìí pín sí àwòrán mọkanla, ọ̀kọ̀ọ̀kan pẹlu ìdojúkọ rẹ̀..
wikipedia
yo
Díẹ̀ lára àwọn àwòrán yìí ni Zureure tàbí ẹnu ọ̀nà àbáwọlé, pẹ̀lú ìṣmoṣe ohun èlò ìbílẹ̀, àwọn odi ìlú àti máàpù ìpínlẹ̀ Kano, ìtàn-akọọlẹ tí Kano, Kano ní Ajeẹ́ńtúrì kọkàn, ogun abẹ́lé, ètò ọrọ-ajé àti orin..
wikipedia
yo
Àyè kan náà ṣí ṣí sílẹ̀ nínú Muṣiọ náà, tó dúró gẹ́gẹ́ bí ìpele iṣẹ́ fún Ijó Kokoroso àti ẹgbẹ́ eré-oníṣẹ́.Ìtàn Ajetúrì Kẹẹ̀ẹ́dógún ni wọ́n kọ́kọ́ kọ́ ilé yìí, fún Muhammad Rumfa, tó jẹ́ ọmọ-ọmọ ọba Hausa, tí wọ́n ṣe fi jẹ Makàmà ti Kano nígbà náà..
wikipedia
yo
Rumfa padà jẹ́ ọba, ó sì kọ́ lọ sí ààfin tuntun, àmọ́ àwọn Makama tí wọ́n wá fi jẹ́ lẹ́yìn ìgbà náà ń gbé ibẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí àwọn ìjọba amúnisìn gba ìlú Kano, ní ọdún 1903, Ilẹ̀yìí jẹ́ ibi tí àwọn aláwọ̀ funfun yìí ń gbé.Muṣió Muṣió mú yìí wà ní òpópónà ààfin Emir, tí wọ́n sì pín sí ayé mọ́kànlá tó ní àwòrán, pẹ̀lú ọ̀kọ̀ọ̀kan tí ó ní ohun-ọ̀ṣọ́ ìbílẹ̀ kan,àwa àwòrán, ohun-èlò orin, àti àwọn ohun Nelo lóríṣiríṣi.Àwọn àwòrán díẹ̀ nínú àwọn ohun ìtàn tí wọ́n tọ́jú ní Gidan Makawón ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ososo je ilu kan ni agbegbe ijoba ibile akoko-Edo, ni ipinle Edo, ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
O ni oju-ọjọ tọ tutu pupọ ti o jo ti Ilu Jos, pẹlu ìwọ̀n gíga ti 1236 lókè ipele òkun..
wikipedia
yo
Pelu iye eniyan to wó 100,000 ati àpapọ̀ iwuwo àwọn olugbe ti 5,111 fun 7km Ra1923, o jẹ ki agbegbe yii jẹ ọkan ninu àwọn ìlú to tobi julọ ni agbegbe ìjọba ibilẹ naa.. naa..
wikipedia
yo
Ósoso ní ẹ̀ka èdè tó yàtọ̀, tí wọ́n ń pè ní Gtìgboyà-Uneme-yekhée, tó jẹ́ ti ìdílé ẹ̀id.Orun pín àwọn ààlà pẹ̀lú Okene sí àríwá, Okpella sí ìwọ̀-oòrùn, Maìke sí ìwọ̀-oòrùn, Ojah sí gugu àti Òga sí àríwá-oòrùn..
wikipedia
yo
O jẹ Ilu Aori laarin Edo ati awọn Ipinle kogi . Awon Apata ni ilu Ososo itọkasi..
wikipedia
yo
Ọláyíwọlá ọ̀labanjì kòkúmọ́, tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ NJC ẹ̀ kọker, jẹ́ olórin Afro-Pop ti Orílẹ̀l-Èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O Mark ise pelu.ibẹrẹpẹpẹṣe aye rẹ won bi koker ni ojo 30, osu May, ni odun1993, ni Ipinle Eko.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Babatunde Rhim, ti oruko inagijẹ re n je Lyta, je olorin orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ó tẹ́wọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú YBNL Nation, ní ọdún 2018, àmọ́ ó kúrò lẹ́yìn èdè-àìyedè tó wáyé láàárín òun àti ẹni tó ni ilé-iṣẹ́ náà, ìyẹn Olamide..
wikipedia
yo
O jade awo-orin olorin marun-un, EP id, ni odun 2019.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
AkinMayokun àwòmilamila (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 28, oṣù December, ní ọdún 1984), tí wọ́n tún mọ̀ sí May d, jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O fìgbà kan wà ní ìtẹwobọ̀wé pẹ̀lú R&B àti Square Records, èyí tí àwọn p-Square.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Miracle Guchi Chike (tí wọ́n bí ní March 24, Ọdún 1998) tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Míbobo jẹ́ ọlọ́rin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrinkalẹ̀, òṣèrékùnrin, oninuure àti onísí́n..
wikipedia
yo
Awon obi re wa lati ipinle Abia, amo ipinle Eko lo dagba si, nibi ti o si ti berel ise re.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
abinlọpọ̀ David Jumbọ̀ tí wọ́n bí ní (February 11, ọdún 1988), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Mr 2kay, jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O fìgbà kan tẹ́wọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú Grafton Entertainment, amo o kuro ni ọdun 2018, lati lọ ṣe idasilẹ ile-iṣẹ orin rẹ, to pe ni better Life Entertainment.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Eniola Akinbo (; tí wọ́n bí ọjọ́ 9 Oṣù December, ọdún 1985), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn Mol sì Niyola, jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Chinonso obìnna Amadi (tí wọ́n bí ní September 1, ọdún 1995) jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrinkalẹ̀ àti àgbọ̀rínjáde..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olórin tó kọ́ ara rẹ̀ níṣẹ́ orin kíkọ, àti bí wọ́n ṣe ń kọláàjáde..
wikipedia
yo
O bẹrẹ iṣẹ yii nigba ti o wa ni Ile-ẹkọ giga ti Covenant University, nibi ti o ti kọ ẹkọ nipa.awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Dafromwunon anozuma Bassey ìwúchukwu, ti opo eniyan mo si nonzo Bassey, to fìgbà kan je Nonso Bassey, je olorin orilẹ-ede Naijiria, akọrinkale, oserekunni ati Modeeli.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
ELátinú Allen (tí wọ́n bí ní 28 March 1986), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Orezi, jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó wá láti ìpínlẹ̀ Delta..
wikipedia
yo
Ó di gbajúgbajà nígbà tó kọ orin tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Rihanna" ní ọdún 2013.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Orits WiLíkì jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó máa ń kọ orin reggae..
wikipedia
yo
Ó di gbajúmọ̀ nígbà tí ó gbé orin kan jáde ní ọdún 1989, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ èrètélation..
wikipedia
yo
Witanki tun jẹ ọmọ ẹgbẹ Musical Copyright Society of Nigeria, eyi to jẹ ẹgbẹ olórogún ti Copyright Society of Nigeria.Àtòjọ Awo orin rẹ̀ èrètélation..
wikipedia
yo
Orlando Julius Aremu Olusanya alamọde, ti gbogbo eniyan mọ si Orlando Julius tabi Orlando Julius Èkéde (ti wọn bi ni 22 September 1943 to si ṣaláìsí ni14 April 2022) jẹ olorin, afunfèrè, olori-ẹgbẹ-orin, ati akọrinkale, to sise po pẹlu afrobeat Music.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Chief Stephen Osita Osabe (ti won bi ni March 17, 1936 to si ṣaláìsí ni May 11, 2007), ti opo Eniuan mo si Osita Osabe, je olorin, to wa lati kàyéfì..
wikipedia
yo
Ọ̀kan lára àwọn orin rẹ̀ tó gbajúgbajà tó kọ ní ọdún 1984 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Osondi òwedindi", èyí tó fi ẹsẹ̀ rẹ̀ múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn orin Oìlú-èdè yìí tó gbajúmọ̀ jù lọ.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Fartúùn Abdisálàan àdán jẹ́ ajàfẹ́tọ́ ti ìlú Somalia..
wikipedia
yo
Òun ni adarí àgbà fún elman Peace and Human Rights Centre.Ìgbésí ayé rẹ̀ àdán dàgbà sí ìlú Somalia..
wikipedia
yo
Ó fẹ́ Elman Ali Ahmed, tó jẹ́ oníṣòwò àti ajàfẹ́tọ́,ọmọnìyàn, tó ń rí ṣètò àlàáfíà..
wikipedia
yo
Àdán Abington Mohammed jẹ́ gbajúgbajà òṣìṣẹ́ ilé-ìfowópamọ́ ti ìlú Kẹ́nyà àti oníṣòwò..
wikipedia
yo
Ó fìgbà kan sin gẹ́gẹ́ bi í adarí àgbà ti Barclays Bank ní ìwọ̀-oorun ti àti West Africa.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àdán Augusto López Hernández (tí wọ́n bí ní September 24, 1963) jẹ́ olóṣèlú ilẹ̀ Mexico, Agbẹjọ́.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àdán jọkọṣews or àdánows (O tí wọ́n bí ní 29 October 1979) jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Mexico, tó tàn mọ́ ìlú Fránsì..
wikipedia
yo
O si tun jẹ òṣèrékùnrin ati adarí-eré.Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀àtòjọ àwọn orin rẹ̀orin àdákọ rẹ̀ l'Idole (also released as el idolo in Spanish) estoy Mal no me sí1930 solo dancing to the Radio would you be Mineawon itọkasi..
wikipedia
yo
Edna àdán Ismail (tí wọ́n bí ní born 8 September 1937) jẹ́ agbẹ̀bí, ajàfẹ́tọ́,ọmọnìyàn, ó sì tún jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ Mínísítà fún ọ̀rọ̀ Ilẹ̀ òkèrè, fún Orílẹ̀-èdè Somalia láti ọdún 2003 wo 2006..
wikipedia
yo
Òun sì ni Ààrẹ ẹgbẹ́ victims of torture.ìbẹ̀rẹ̀pe ayé rẹ̀ ìlú Hargé ni wọ́n bí Ismail sí, ní 8 September 1937, ó sì jẹ́ ọmọ oníṣègùn kan..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ márùn-ún tí ìyá rẹ̀ bí, amo méjì kú nínú wọn jáè ibi wọn.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Awọn ohunfukì ka ẹ̀bẹ fun oṣelu awọn eto, ti a npè ní petítọn no..
wikipedia
yo
30, Jẹ akoko ẹbẹ ninu eyi ti Mohamed Seghir Oorunton beere awọn Oṣelu Awọn eto ti Algerians ni French Algeria lẹhin ti awọn 1919 idalẹnu Ilu idibo ni Algiers.Itan-akọọlẹ Ikopa ti ẹgbẹẹgbẹrun awọn ọmọ ogun Algeria ninu awọn ogun ti Ogun Agbaye akọkọ ni Faranse ati idasi ipinnu wọn ni iṣẹgun si Imperial German Army jẹ ere wọn lẹhin ipadabọ wọn si Algeria.O jẹ ni ọna ti Òfin Jnna gba awọn ogbó ati awọn ọmọ abinibi aláàbò laaye lati gba awọn iṣẹ ni iṣakoso amunisin ati lati gba ohun-ini gidi ni awọn ilu ati ni igberiko gẹgẹbi ami ìsọdọmọ laarin ilana ti kóòdù indigeNat.Awọn ipese ti o tẹle ifowosi ofin ni ọjọ 4 Oṣu Keji ọdun 1919 jẹ ki o ṣee ṣe lati gbejade awọn ọrọ ofin ti n ṣalaye awọn Iṣowo ti a gba laaye si awọn ara ilu Algerian pẹlu awọn ihamọ nitori abajade ninu awọn ipo alamọdaju ti iṣakoso.bibẹẹkọ, awọn idibo ilu ti ọdun 1919 jẹ ki awọn aṣoju iṣelu ti awọn ara ilu lati faagun ni awọn agbegbe gẹgẹ bi eto, nitorinaa o ṣe agbejade iwulo tuntun fun awọn ominira iṣelu ati ẹgbẹ.Nítòòtọ, Igbimọ Gbogbogbo Khad Ibn Rhim ni Algiers, ati Igbimọ Ilu Mohamed GGGG Oorunkekì gẹgẹbi Aṣoju ti awọn ara ilu ti a yan, bẹrẹ lati .. ati ki o ṣe agbekalẹ igbese nipasẹ nipasẹ awọn ile-iṣẹ Faranse ti o wa lati awọn agbegbe si Alàgbà Faranse, ati paapaa titi di ìsisìyí..
wikipedia
yo
30", Igbimọ, ti Oludari nipasẹ agboyágágá Charles Cadil, níparí sọ ni odi lori ero nipa awọn eto oṣelu ti o gbooro fun awọn abinibi, ati kikọ ati kikọ ti tẹ̀ sinu awọn iforukọsilẹ..
wikipedia
yo
Raymond Ablack (tí wọ́n bí ní November 12, 1989) jẹ́ òṣèrékùnrin àti apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè Canada..
wikipedia
yo
O bẹrẹ iṣẹ rẹ ni ọdun 2000, gege bi i oṣeremode, lori itage, to si ṣe ẹda-itan Young Simba ninu The Lion King ni Princess of Wales Theatre.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
James William Acaster (; tí wọ́n bí ní 9 January 1985) jẹ́ apanilẹ́rìn-in ti ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Kade Adams tabi Kev' Adams (ti orukọ àbísọ rẹ̀ n jẹ́ Kevin Mamadja; 1 July 1991) jẹ́ apanilẹ́rìn-in ilẹ̀ Fránsì, òṣèrékùnrin, àti Asagbéjáde fíìmù.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Pamela Fionna Adlon Kaka (tí wọ́n bí ní July 6, 1966) jẹ́ òṣèrébìnrin ti orílẹ̀ èdè America..
wikipedia
yo
Ó gbajúgbajà fún lílò ohun rẹ̀ láti fi ṣe Ẹda-itan Bobby Hill nínú Fíìmù King of the Hill (1997-2010).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo