cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ibi ti ayọ̀ yí ti sẹ̀wà ní agbègbè Charanga, tí ó wà ní ibi tí ó di orílẹ̀-èdè India loni ní nkan bí ọ̀rúndún karùn ún sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Àmọ́ òfin àti ìlànà títa ayọ̀ náà tí à ń lò títí di òní ni wọ́n gbé kalẹ̀ ní Yúróòpù ní nkan ní ọ̀rúndún kéje sẹ́yìn tí gbogbo ayé sì tẹ́wọ́ gba òfin àti ìlànà yí títí di ìparí ọ̀rúndún kọkàndínlógún ..
wikipedia
yo
lọni, Chess jẹ ayo ti o gbaju-gbaja julo kaakiri agbaye ti oke àìmọye eniyan si n fi ayo naa ṣere opolo..
wikipedia
yo
Ayọ̀ Chess jẹ́ ayọ̀ tí a ń fi ọgbọ́n inú ta tí ó sì àwòrán pẹ̀lú ìlànà tó mọ́yánlórí tí kò sì ní ọ̀nà àlùmọ̀kọ́rọ́yí kankan..
wikipedia
yo
Lórí aya ayọ̀ ni a ti ma ń rí àwọn ọmọ ayò tí wọ́n jẹ́ mẹ́rìndínlógún ní apá ìkọ́ kọ̀ọ̀kan ma ń tò ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́ ní ìwọ̀n 8x8..
wikipedia
yo
Onta kọ̀ọ̀kan ma ń dari ọmọ ayò mẹ́rìndínlógún tí wọ́n ń pè ní Chess piece..
wikipedia
yo
Ninu àwọn ọmọ ayọ̀ yí ni a ti má ń rí ọba, olórí, rọòkú meji, baàóobú meji, naìtí meji, ati àwọn ọmọ ogun kékèké mẹjọ tí wọn ń pè ní pawns..
wikipedia
yo
Nínú ìlànà títa ayọ̀ yí, ọ́nta tí ó bá mú ìkó funfun ni yóò kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ títa ayọ̀ kí ọnta kejì tí ó mú ikọ̀ ọmọ ogun dúdú ó tó tà tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Ẹnikẹ́ni nínú àwọn òǹta méjẽjì yí ni ó le pa ọba pẹ̀lú dídé pàkúté láti fi pa ọba àti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ lójú ọpọ́n..
wikipedia
yo
Ayọ̀ yí lè parí pẹ̀lú pípa ọba tàbí kí wọ́n ta omi níparí ìdíje ayọ̀..
wikipedia
yo
Gbígbé ìdíje ayò Chess kalẹ̀ ni ó bẹ̀rẹ̀ ní àárín ọ̀rúndún kọkàndínlógún nígbà tí àjọ Fide (The International Chess Federation) ń ṣe àbójútó ìdíje eré ìdárayá yí..
wikipedia
yo
Ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ gba adé World Chess Champion, ni Wilhelm Steini ní ọdún 1886; nígbà tí ẹni tí ó di àmì-ẹ̀yẹ náà mú lọ́wọ́ báyĩ ní ding Liren..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1997, deep Blue ni ó jẹ́ kọ̀mpútà àkókò tí yóò gbadé ẹni tí ó mọ ayò Chess tà jùlọ lágbàáyé nígbà tí ó fgbára alátakò rẹ̀ GARRY Kasv tí òun náà jẹ́ Kótà gbolẹ̀..
wikipedia
yo
Láyé òde òní, ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà ti di àgbàọ́ nínú kí a ta ayò Chess ju ọmọnìyàn lọ lágbàáyé..
wikipedia
yo
Èyí náà sì mú ìdàgbà-sókè bá ìlànà, àgbékalẹ̀, títa ayọ̀ náà lágbàáyé.Àwọn òfin rẹ̀òfin àti ìlànà tí ó de títa ayò yí ní àjọ Fide (Federation internatioṣùàwọn des èchecs; "International Chess Federation"), tí wọ́n ṣe agbátẹrù fún eré ìdárayá yí lágbàáyé ti gbé kalẹ̀ nínú ìwé kan tí wọ́n pè ní Handbook..
wikipedia
yo
ọ̀nà méjì ni a máa n gbà dá àwọn ọmọ inú Chess mọ́ ní wíwo onírúurú èyí tí ó jẹ́ tàbí àwọ̀; èyí ni àwọ̀ funfun àti àwọ̀ dúdú, tí a tún lè pè ní ṣèèṣì aláwọ̀ dúdú àti funfun..
wikipedia
yo
àwọn ẹni tí wọ́n n ta Chess ní alẹ́ lẹ́ ni olùta ṣèèṣì tàbí Aláyọ̀, bákan náà ni àwọn ọmọ inú ṣèèṣì jẹ́ funfun tàbí dúdú..
wikipedia
yo
a máa ń ta ayọ̀ ṣèèṣì lórí pákó onígun mẹ́rin tí ó ní row mẹ́jọ, column mẹ́jọ..
wikipedia
yo
Nípa àpéjọpọ̀, àwọn onígun mẹ́rin ti ojú lílà rẹ̀ jẹ́ mẹ́rìnlélọ́gọ́ta ní àwọ̀ oríṣi méjì tí ó jẹ́ funfun àti dúdú; àwọn àwo tí ó wọ́pọ̀ fún ayọ̀ ṣèèṣì jẹ́ funfun àti brown, tàbí funfun àti àwọ̀ ewé.Àwọn ọmọ inú ayọ̀ ṣèèṣì ni ó wà ní ojú àwòrán yìí ní òkè..
wikipedia
yo
Àwọn àwọ̀ dúdú sì wà ní òdìkejì bí àti tó funfun, tí ó sì jẹ́ ìkanáà ..
wikipedia
yo
pákó ṣèèṣì náà wà ní apá ọ̀tún tí ó súnmọ́ ọwọ́ aláyọ̀..
wikipedia
yo
Ipò tí ọba àti olórí gbọ́dọ̀ wà ìbámu pẹ̀lú ọ̀rọ̀ kan tí wọ́n máa ń sọ pé “Olórí lórí ayé rẹ̀”, tí ó túmọ̀ sí pé olórí funfun lórí àwọ̀ funfun, olórí dúdú lórí àwọ̀ dúdú).Nínú ìdíje, àwọn olùṣètò ìdíje ni wọ́n yóò fún àwọn olùdíje ní ọmọ ayọ̀ ṣèèṣì; tí ó bá jẹ́ fún ìdárayá lásán, àwọn olùta a máa lo sísọ coin sókè, tàbí kí wọ́n fi pawn dúdú àti funfun sí ọwọ́ méjejí kí àwọn olùta mú ní ọ̀kọ̀ọ̀kan, èyí tí oníkálùkù bá mú ni wọn yóò fi ta ayò náà.Bí a ṣe ń gbé ayọ̀funfun ni yó kọ́kọ́ gbéra, lẹ́yìn ti àwọn ìyókù ó sì tẹ̀lé, wọ́n sì ma ń gbéra ní kọ́kàn..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ta ayọ̀ yìí lè gbé ayọ̀ náà sí ojúgun tí ayọ̀ míràn kò sí tàbí ibi tí ayọ̀ olùtako wà, eléyìí á sì mú kí a yọ ayọ̀ náà kúrò..
wikipedia
yo
Kí kúrò láti ojúgun kan sí òmíràn ṣe pàtàkì; ẹni tí ó tayọ gbọdọ̀ gbé ọ̀kan lára àwọn ayọ̀ rẹ̀ síbo míràn lẹ́yìn tí olùtako rẹ̀ ti gbé ayọ̀..
wikipedia
yo
Ọba jẹ́ ayọ̀ tí ó lágbára jù, ó sì ṣe pàtàkì fún olùtako láti sa ipá láti yọ ọba alátakò rẹ̀ nínú ẹrẹ̀, èyí lè mú kí ó jáwé olúborí nínú eré ayọ̀ náà..
wikipedia
yo
Gori le lo ibi ti o fẹ ṣugbọn ko le gba ori ayo miran koja..
wikipedia
yo
bishop náà le lọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ojúgun tí ó fẹ́ nípa lílọ sọ́tùn sósì ṣùgbọ́n kò lè gba orí àwọn ayọ̀ míràn kọjá..
wikipedia
yo
Queen ní lè ṣe àwọn nkan ti interpret àti Bishop le ṣe ṣùgbọ́n kò lè gba orí àwọn ayọ̀ míràn kọjá.
wikipedia
yo
A Knight lè lo ojúgun tí ó sún mọ́ sí, òún nìkan sì ni ayọ̀ tí ó lè gba orí ayọ̀ míràn kọjá..
wikipedia
yo
pawn náà lè lọ sí ojúgun míràn tí ayọ̀ kò sí.Pípa ọmọ ayònígbà tí ọba bá wà ní inú ewu, wọ́n á sọ wípé Check..
wikipedia
yo
ọ̀nà tí ọba lè gbà bọ́ lọ́wọ́ ewu ni kí ó o kúrò ní ojú ibi tí ó wà kí ẹ̀mí rẹ lè dé..
wikipedia
yo
Ọ̀nà mẹta ni wọ́n lè gbà bọ́ lọ́wọ́ ewu kí ó sì já padà..
wikipedia
yo
A Move in response to a Check is Legal only if it results in a position where the king is no longer in Check..
wikipedia
yo
It is never legal for a player to make a move that puts or leaves the player's own king in Check..
wikipedia
yo
In casual Games, it is common to announce "Check" when put the opponent's king in Check, but this is not required by the Rules of ss and is usually not done in tour:“Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Josh James Brolin (; tí a bí ní Ọjọ́ kejìlá Oṣù Kejì Ọdún 1968) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.Josh jẹ́ ọmọ James Brolin, ó sì di gbajúmọ̀ nígbà tí ó ṣeré nínu fíìmù The Gooes (1985)..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọdún, Brolin tún ṣeré nínú fíìmù No Country for Old Men (2007)..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2022, Brolin ṣere ninu fiimu Outer range.Awọn itọkasi..
wikipedia
yo
DiKevina Michelle Wright (tí a bí ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹwa Ọdún 1993) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Guyana mo Britain..
wikipedia
yo
O bẹrẹ iṣẹ oṣere pẹlu awọn fiimu bi Top Boy, Coming Up, Chasing Shadows, Adu, Doctor Who, ati Black Mirror..
wikipedia
yo
Wọ́n yan sí ara àwọn tí ó tọ́ sí àmì-ẹ̀yẹ Primetime Emmy Award..
wikipedia
yo
Ó di gbajúmọ̀ nígbà tí ó ṣeré nínu fíìmù Urban HyAdonijah tí ó jáde ní ọdún 2015, èyí tí ó sì gba àmì ẹ̀yẹ British Academy of Film and Television Arts (BAFTA) fún.Ní ọdún 2018, ó di gbajúmọ̀ káàkiri orílẹ̀ èdè nígbà tí ó kó ipa SHuri nínu fíìmù Marvel Cinematic Universe, Black Panther, èyí tí ó sì gba àmì ẹ̀yẹ NAACP Image Award àti Sa Award fún..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, ó gba àmì-ẹ̀yẹ BAFTA Rising Star Award..
wikipedia
yo
O tun ko ipa ninu small axe, eyi ti o si gba ami-eye Satellite Award fun.Awọn itọkasi..
wikipedia
yo
YouTube jẹ́ pínpín fídíò orí ayélujára ti Amẹrika ati ipilẹ ẹrọ àwùjọ àwùjọ ti o wa ni San Bruno, California, Amẹrika..
wikipedia
yo
wiwọle si agbaye, ti ṣe ifilọlẹ ni Kínní 14, 2005, nipasẹ Steve chen, Chad Hurleyley, ati jawed Karim..
wikipedia
yo
O jẹ ohun ini nipasẹ Google ati pe o jẹ oju opo wẹẹbu keji ti a ṣabẹwo julọ, lẹhin wiwa Google..
wikipedia
yo
YouTube ni diẹ ẹ sii ju 2.5 bilionu awọn olumulo oṣooṣù, ti o n wo awọn fidio ti o ju bilionu kan lọ lójoojúmọ́..
wikipedia
yo
Ni Oṣu Karun ọdun 2019, awọn fidio ti n gbejade ni iwọn diẹ sii ju awọn wakati 500 ti akoonu fun iṣẹju kan.Ni Oṣu Kẹwa ọdun 2006, Google ra YouTube fun $1.65 bilionu..
wikipedia
yo
Ohun ini Google ti YouTube faagun awoṣe iṣowo aaye naa, ti n pọ si lati jijẹ ọwọ-wiwọle lati awọn ipolowo nikan si fifun akoonu wiwa gẹgẹbi awọn fiimu ati akoonu iyasọtọ ti YouTube ṣe..
wikipedia
yo
O tun funni ni ere YouTube, aṣayan ṣiṣe alabapin ṣiṣan fun wiwo akoonu laisi ipolowo..
wikipedia
yo
YouTube tun fọwọsi awọn olupilẹṣẹ lati kopa ninu eto ADSe Google, eyiti o n wa lati ṣe ina ọwọ-wiwọle diẹ sii fun ẹgbẹ mejeeji..
wikipedia
yo
YouTube royin wiwọle ti $29.2 bilionu ni ọdun 2022..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2021, owo-wiwọle ipolowo ọdọọdun YouTube pọ si $28.8 bilionu, ìlọsókè ninu owo-wiwọle ti 9 bilionu lati ọdun iṣaaju.Níwọ̀n rira rẹ nipasẹ Google, YouTube ti fẹ siwaju si oju opo wẹẹbu pataki sinu awọn ohun elo kakà, tẹlifisiọnu nẹtiwọọki, ati agbara lati sopọ pẹlu awọn iru ẹrọ miiran..
wikipedia
yo
Awọn ẹka fidio lori YouTube pẹlu awọn fidio orin, awọn agerisi fidio, awọn iroyin, awọn fiimu kukuru, awọn fiimu ẹya, awọn orin, awọn iwe itan, awọn Tirela fiimu, awọn Teurs, awọn ṣiṣan ìfìwé, awọn Vlogs, ati diẹ sii..
wikipedia
yo
Pupọ akoonu jẹ ipilẹṣẹ nipasẹ awọn ẹni-kọọkan, pẹlu awọn ifowosowopo laarin YouTubers ati awọn onigbọwọ ajo..
wikipedia
yo
Awọn ile-iṣẹ media ti iṣeto bi Disney, Paramount, NBCUniversal, ati Warner Bros..
wikipedia
yo
Àwárí ti tún ṣẹ̀dá àti faagun àwọn ìkànnì YouTube àjọ wọn lati polówó si olùgbọ́ nla.YouTube ti ni ipa àwùjọ ti a kò tii ri tẹ́lẹ̀, ni ipa lori aṣa olokiki, awọn aṣa Íńtánẹ́ẹ̀tì, ati ṣiṣẹda awọn olokiki Oloye-pupọ..
wikipedia
yo
láìbìkítà ìdàgbàsókè àti àṣeyọrí rẹ̀, ó ti ṣofintoto púpọ̀ fún ẹ̀sùn ní ìrọ̀rùn ìtànkalẹ̀ àlàyé tí kò tọ́ àti pínpín àkóónú ti aláìjí, ìlòdì sì ni ìgbàgbogbo àwọn àṣírí àwọn olumulo rẹ̀, ṣíṣe ìhàmọ̀n múu, àti fífi ààbò àti àlãfíà ọmọ léwu, àti fún àwọn ìtọ́sọ́nà rẹ̀ àti bíi wọn ṣe ṣe ìmúṣẹ...
wikipedia
yo
Ṣímú Liu ( ; ; tí a bí ní ọjọ́ kàndínlógún oṣù kẹrin ọdún 1989) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Kánádà..
wikipedia
yo
O gbajumọ fun kiko ipa Shang-chi ninu fiimu Marvel Cinematic Universe, Shang-chi and the legend of the Ten rings ti o jade ni ọdun 2021..
wikipedia
yo
Ó tún kó ipa gẹ́gẹ́ bi Jung Kim nínu fíìmù CBC Television Kim's conveni ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ Actra Award àti Canadian Screen Awards fún ipa rẹ̀ nínú Blood and Water.ní ọdún 2022, Liu kọ ìwé we Were Wereds, Time sí pé ẹ ní ara àwọn òṣèré ọgọrun-un ti o gbajumọ jùlọ ní àgbáyé.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Benjamin Geza AFRIXck (ti a bi ni ojo keedogun Oṣu Kẹjọ ọdun 1972) jẹ oṣere ati ase fiimu ọmọ orilẹ ede Amẹrika..
wikipedia
yo
Ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Awards fún àwọn fíìmù rẹ̀..
wikipedia
yo
AFRIXX bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣeré láti ìgbà èwe nígbà tí ó ṣeré nínu eré pbs tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ The Voyage of the Och (1984, 1988)..
wikipedia
yo
Ó tún padà ṣeré nínú Dazed and Confused (1993) àti àwọn eré àwàdà míràn tí Kevin Smith ṣe, àwọn eré bí Chasing Amy (1997).AFRIXck tún gbajúmọ̀ sí nígbà tí òun àti Matt Dámọn gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Award for Best Original Lóòótọ́ fún kíkọ Good Will hunting (1997)..
wikipedia
yo
O tun ṣere ninu awọn fiimu bi ArmaMAMAMA (1998), Pearl Harbor (2001), the sum of all fears ati Changing lanes (both 2002)..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó dàbí pé iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré fẹ́ ma lọ́lẹ̀, ó tún padà sọ jí nígbà tí ó kó ipa George Reeves nínú fíìmù Hollywoodland (2006), ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ Volpi Cup for Best Actor.Àwọn eré tí ó ti darí ní Gone Baby Gone (2007), The Town (2010) àti Argo (2012).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Abadam jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọba ìbílẹ̀ ìjọba ìbílẹ̀ ìpínlẹ̀ Borno, Naijiria, ní apá ìwọ̀ oòrùn Lake Chad..
wikipedia
yo
Awon ala re ni Chad ati Niger, o si sun mo Cameroon, ni odun 2016, awon olugbe rẹ to 140,000 olu ilu re wa ni Mãfatori..
wikipedia
yo
Ètò àbò àti Ìlera Ara wà lára àwọn ìdojúkọ ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Abadam..
wikipedia
yo
Jared Joseph lètò ( ; tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1971) jẹ́ òṣèré àti olórin ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O ti gba ọpọlọpọ ami-eye ninu iṣẹ oṣere ti o ti n ṣe fun ọpọlọpọ ọdun, awọn ami ẹyẹ bi Academy Award ati Golden Globe Award..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú pẹ̀lú, ó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ orin kíkọ gẹ́gẹ́ bí ara àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Rock band Thité Seconds tó Mars.Lẹ́yìn ìgbà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré nínu fíìmù My So-called Life (1994), lètò ṣeré nínu How to Make An American Quilt (1995), Ó sì gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínu fíìmù Prefọ́nrtion (1997)..
wikipedia
yo
O tun ṣere ninu awọn fiimu bi The Rite Red Line (1998), Fight Club (1999), Girl, Interrupted (1999) ati American Sysy (2000)..
wikipedia
yo
létò gba ọpọlọpọ ìyìn ipá rẹ̀ ninu rẹ̀quiem for a Dream (2000)..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó bẹ̀rẹ̀ sí ń gbajúmọ̀ iṣẹ́ orin kí ó tó padà sí iṣẹ́ òṣèré pẹ̀lú panic room (2002), Alexander (2004), Lord of War (2005), Chapter 27 (2007), àti Mr..
wikipedia
yo
O gba ami-eye Academy Award for Best Supporting Actor fun ipa rẹ ninu Dallas Buyers Club (2013)..
wikipedia
yo
Laarin odun 2016 si 2022, o ṣere ninu awon fiimu bi suicide Squ (2016), Blade runner 2049 (2017), The Little Things (2021), House of Gucci (2021), ati Morcasal (2022).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
TERENCE Henry Stamp (tí a bí ní Ọjọ́ kejìlélógún Oṣù Keje Ọdún ) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi alatako nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré..
wikipedia
yo
O gba ami-eye Golden Globe Award, Cannes Film Festival, ati Silver Beasi won si yan kun ara awon ti o to fun ami-eye Academy Award ati BAFTA Awards meji.leyin igba ti o ko eko gboye ni ile eko ere Webber Douglas Academy of Dramatic art ni London, o bere ise osere ni odun 1962..
wikipedia
yo
Fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀, mú kí ó gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Award àti BAFTA fún Best Newcomer..
wikipedia
yo
O ṣere pẹlu oṣere Christie ninu ere Far from the madding crowd (1967)..
wikipedia
yo
Ó tún gbajúmọ̀ sí nígbà tí ó kó ipa General Zod nínu eré Superman (1978) àti Superman II (1980)..
wikipedia
yo
Ipa re ninu ere The Adventures of Priscilla, Queen of the Desert (1994) mu ki o gba ami-eye BAFTA Award o si tun mu ki won yan mo ara awon ti o to si ami eye Golden Globe Award..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó ṣeré nínu eré The Limey (1999) èyí tí ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ Independent Spirit Award fún..
wikipedia
yo
Brandon James Routh (; tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án Oṣù Kẹwa Ọdún 1979) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O ṣere Superman ninu fiimu 2006 Film Superman returns, eyi ti o mu ki o gbajumọ kaakiri orile ede..
wikipedia
yo
O tun ko ipa Daniel Shaw ninu fiimu NBC ti akori re je 1988..
wikipedia
yo
Ara àwọn eré míràn ti Routh ti kópa ní Zack and mirí Make a Porno àti Scott Pilgrim Vs..
wikipedia
yo
The World.Ní ọdún 2014, ó kó ipa Ray Palmer / The àtòm nínu eré Arrs..
wikipedia
yo
Antje Traue (; ti a bi ni ojo kejidinlogun osu kinni odun 1981) je osere omo orile ede Jamani..
wikipedia
yo
O ṣere ninu fiimu Gẹẹsi fun igba akọkọ nigba ti o ṣere ninu Pandorum..
wikipedia
yo
Ó di gbajúgbajà káàkiri àgbáyé nígbà tí ó ṣeré nínú gẹ́gẹ́ bí fàọ̀rá nínú fíìmù Man of Steel (2013) àti The Àsh (2023), àti gẹ́gẹ́ bi Agnes níelsen nínú eré Netflix kan tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Dark.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
William gaither Cressyp (; tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ Oṣù Keje ọdún 1968) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ipa rẹ̀ nínu fíìmù Jesus' Son (1999) jẹ́ kí wọ́n yàn mọ́ àwọn tí ó tọ́ sí Independent Spirit Award for Best Malelé Lead..
wikipedia
yo
Cgbọ́rọ̀n gba ami-eye Tony Award fun ipa re ninu fiimu Tom Stoppard ti akori re je the Coast of Upia (2007)..
wikipedia
yo
O tun ti ṣere ninu awọn ere bi Gypsy (2017), The morning show (2019), eyi ti o mu ki o gba ami-eye Primetime Emmy Award ati Critics' Choice Television Award.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Adewale Akinnuoye-Agbaje (; ti a bi ni ojo kejilelogun osu kejo odun 1967) je osere omo orile ede Naijiria ti opolopo mo fun ipa re gege bi Simon Adebisi ninu ere Oz, Mr..
wikipedia
yo