cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Joshua ni “Àdánù nla si Kristianiti” Lohin ti o ku ni ọdun 2021.O tun wa ninu igbasilẹ pe Isaiah ogédégbé yin igbesi aye t..
wikipedia
yo
Joshua ní June 13, 2023.Ijagbara Kọkànlá Oṣù Keje ọdún 2014 ni orúkọ Isaiah ogédégbé wà nínú ìròyìn nígbà tó kọ oríkì nípa kẹfèéfèé.Ní ọjọ́ mẹ́rìndínlógún oṣù kejì ọdún 2018, orúkọ Isaiah ógedegbe tún wà nínú ìròyìn nígbà tí ó gba Kẹ́mi Ọmọ-lọ́lù-lo nímọ̀ràn.Ní ọjọ́ 9 oṣù kẹfà ọdún 2020, orúkọ Isaiah ógédégbé tún wà nínú ìròyìn nígbà tí ó òfintótó pípa George Flo. Ní ọjọ́ 29 Oṣù Kẹsan ọdún 2022, Isaiah ògédégbé kọ oríkì kan láti yin ìgbé ayé Nelson Mandela.A ti lo àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Isaiah ogedegbe láìsí orúkọ ra.Ní ọjọ́ 27 oṣù kejì ọdún 2017, ìjábọ̀ kan nípa Warri Times kéde àrán ti plagia kan.Ni ọjọ́ 3 Oṣù Kẹfà kẹfà ọdún 2023, Isaiah o òfintótó plavrism, ó sì àpèjúwe bí olè jíjà.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Awọn ojutu ounjẹ miiran ko ni anfani lati pese gbogbo awọn idahun ìjẹẹmu pataki wọnyi..
wikipedia
yo
Nítòótọ́, àwọn àpótí kò ṣàkóso láti pèsè àwọn oúnjẹ tó ṣe pàtàkì sí ìwọ̀ntúnwọ̀nsì tó dára ti ajá..
wikipedia
yo
Níti ohun tí a pè ní oúnjẹ titun, kò tọ́ ní gbogbogbo nítorí pe o nílò lati jẹ ìwọ̀n lilo ni ọ̀nà ti o ni oye pupọ lati di ounjẹ Ilera ati ìwọ̀ntúnwọ̀nsì..
wikipedia
yo
Ìjẹ́ẹ́ dídára tó gaju yóò gbà ọ́ láàyè láti fún ajá rẹ ohun gbogbo tí ó nílò láti gbé dáradára àti ọjọ́ orí dáradára.Ṣàkóso àwọn ẹranko rẹ lórí R'oko Troxy2..
wikipedia
yo
Ní àówá tí ajá rẹ̀° ojú àti eti nínúó gbọ́dọ̀ tó àwọn agbègbè méjì wọ̀nyí ní pàtàkì nítorí pé wọ́n ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ìdàgbà àwọn Germs..
wikipedia
yo
Yẹra fún lílo omi fún irú mímọ́ yìí ṣùgbọ́n fẹ́ àwọn ìpara/ago ti Ph tí ó súnmọ́ ti ajá rẹ. páádi àti Claws– nigbagbogbo ṣàyẹ̀wò ipo tí àwọn páádi ajá rẹ̀ kí ó gé irun tí ó dàgbà níbẹ̀..
wikipedia
yo
Nitòótọ, àwọn páádi náà jẹ́ ifarabalẹ púpọ̀ àti pé ó tún ní ìtara sí Absces àti àwọn àwọn àkóràn Olú..
wikipedia
yo
Ni iru ti ikolu, kan si Alagbawo rẹ Uaniari.- idagba ti Claw ni iyara, o le pari si atunṣe ati ipalara aja rẹ ni ipele ti páádi naa..
wikipedia
yo
Èyí ni ìdí tí ó ṣe pàtàkì púpọ̀ pé kí ó rántí láti gé àwọn Claws rẹ̀ tí ajá rẹ̀ bá gbé díẹ̀ (ní òtítọ́, rìn ní ọ̀nà tí ó dára jùlọ láti wo àwọn Claws)..
wikipedia
yo
kukuru, wọn yoo ran aja rẹ lọwọ lati lọ kiri ati ki o ṣe idiwọ fun u lati ni ipalara. awọ ati irun- fọ aja rẹ nigbagbogbo lati yọ irun ti o ku ati idoti kuro..
wikipedia
yo
Àwọn ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí BRusing dá lórí àwọn ẹ̀yà sí èyí tí rẹ̀ àjà jẹ́ ti (kúkúrú, gùn, lílé, dan ìrun...) tí ajá rẹ̀ bá ní kúkúrú tàbí gun irun, BRusing yẹ kí ó wá ojoojúmọ́..
wikipedia
yo
Tí ajá rẹ̀ bá jẹ́ gíbo-Ide, wòólly tàbí kukuru-irun ajá, BRusing yẹ kí ó ṢEÉ ṣe lẹ́ẹ̀kan tàbí léméjì ní ọ̀sẹ̀ kan..
wikipedia
yo
Sugbon Sora, botilẹjẹpe igbohunsafefe ti iwe da lori ijade ọsin rẹ ati awon isere ere (igbohunsafefe yato lati ose 2 si 6), maṣe we nigbagbogbo nitori pe, ninu ọran yii, Sebum aabo ti ewu rẹ ti yọkuro ati ipa ìgbóná rẹ ti yipada..
wikipedia
yo
Yan kan pato, RídPulu ti o ni agbara giga (ti kii se ibinu, ti o bọ̀wọ̀ fun Ph ajá rẹ) ti yoo dáàbòbò awọ ara rẹ daradara..
wikipedia
yo
Máṣe lọ Rídṣánì rẹ̀ ṣùgbọ́n nígbàgbogbo RídPulu kan pàtó fún àwọn ajá nítorí ajá rẹ̀ ni Ph tí ó yàtọ̀ púpọ̀ sí tirẹ̀..
wikipedia
yo
Yàgò fún àwọn RídPulu gbígbẹ́ tí ó ní òpin iṣẹ́ ṣíṣe mímọ́.Ṣàkóso àwọn ẹranko rẹ lórí R'oko Troyó..
wikipedia
yo
Darlington Mwọkọ̀cha jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó jẹ́ aṣojú agbègbè Ábíá Central Federal láti ọdún 2023..
wikipedia
yo
Kí ó tó di Senato, ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ilé Ìgbìmọ̀ asòfin kékeré tí ó sojú Isiala-ngwá North/Isi-Ala-ng South laarin 2015 si 2019..
wikipedia
yo
Mwọkọ̀cha jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Ábíá State House of Assembly láàrín 2007 sí 2015.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Isọ̀pọ̀ Elisha Abbo (tí a bí ní múbi North, Nàìjíríà) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun ni Senato ti o n se asoju agbegbe Adamawa North Senatorial District ni Ipinle Adamawa..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òsèlú All Progressives Congress (APC) lọ́wọ́ lọ́wọ́.ipa rẹ̀ nínú òsèlúni ọjọ́ kẹtàlélógún Oṣù Kejì ọdún 2019, wọ́n yan Abbo gẹ́gẹ́ bí Senato tí ó ń sojú agbègbè apá Ariwa adáwa, Iye àwọn tí ó dìbò fún tó 79,337. Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Bako Dáúdà yarọe jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Senato tí ó ń sojú agbègbè adáwàwá South Senatorial District ti Ìpínlẹ̀ adáwà ní Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà lọ́wọ́lọ́wọ́.Ìpìlẹ̀ rẹ̀ wọ́n bí Binos dáṣé òmìnirae ní ọjọ́ kínní oṣù kínní ọdún 1955, ní WaGole, abúlé kan ni agbègbè rìbádu Ward ti Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìbílẹ̀-wa ní Ìpínlẹ̀ adáwàwá, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Gírémbiya Joshua, ni ọdun 1983; wọn bi ọmọ mẹrin.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
gTẹ́nìwalàdá jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọba ìbílẹ̀ ní Federal Capital territory, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Glisitiwa ní ilé tí ó tó 1,0km km àti olùgbé 157,770 ní ìgbà ìkànìyàn ti ọdún 2006..
wikipedia
yo
kí wọ́n wọ́n tó dá Gvaowa kalẹ̀, ó wà lábẹ́ agbègbè Kwali ti Abuja tẹ́lẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àwọn abìdí Braille jẹ́ ètò kíkọ́ fún afọ́jú tí a fi owó kà..
wikipedia
yo
Warri Times ni aaye ayelujara ti Isaiah ogédégbé ni Warri..
wikipedia
yo
Onkiwe Ńlá Amuẹrika kan Frederic will mu nuba Warri Times ninu iwe 2017 ro.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
pedace jẹ́ ìkànnì ayélujára tí ó jẹ́ ìní ilé iṣẹ́ mẹ́ta..
wikipedia
yo
Awon ti o n lo o de iye Milionu ọgọrin ni aarin wakati mejidínlãdọ́ta.won fi ikanni Thje lele ni ojo karun-un osu keje ni ogorun-un orile ede, awon orile ede bi United States, United Kingdom, Australia, New Zealand, Canada, ati Japan.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Mai Mala buni tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàn Oṣù kọkànlá ọdún 1967 jẹ́ olóṣèlú tí ó ti ṣe Gómìnà éí ní Ipinle Yobe] ní ọdún 2019 àti Oọ̀m L'rílé-èdè Nàìjíríà.Òun Nó wọn dìbò yàn nínú ìyìn tó wáyé ní ọdún 2019 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress..
wikipedia
yo
Ṣaaju ki o di gomina ni o tinwa nipo Akowe Agba fun egbe Osele naa.ibẹrẹ aye ati ẹkọ rẹ wọn bi buni ni ojo kokandinlogun Oṣu kọkanla ọdun 1967 ni agbegbe binu gárì ni Ipinle Yobe .binu bẹrẹ eko ikẹkọ ile-kẹ̀ù lati kọnipa imo àlùkùránì labẹ olukọ rẹ ti o tun jẹ baba rẹ..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ nílé ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti buni gàrí níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1979..
wikipedia
yo
O wọle Eko oniwe mewa ti ijoba ti o wa ni Goni ni ọdun 1979, leyin ti o pari eko alakoobere rẹ, ti o jade gbàwé ẹri iwe mewa ni ọdun 1985.buni tun wole Eko Fasiti Ibra formation ti o wa ni orile-ede Benin Republic lati ko nipa imo International Relation ti o si jade ni ọdun 2014..
wikipedia
yo
nìkan náà ni ó gba ìwé ẹ̀rí Master láì ilé-ẹ̀kọ́ Leeds Bedun University, ní United Kingdom.Ọjọ́ rẹ̀látàrí ìmọ̀ nípa iṣẹ́ Ìrìnkèrindò ọkọ, ti jẹ́ iṣẹ́ kan pàtàkì nínú ẹbí rẹ̀ ni ó jẹ́ kí ó tètè jí gìrì sí òwò ṣíṣe..
wikipedia
yo
Èyí mú kí ó lọ kẹ́kọ̀ọ́ nípa iṣẹ́ ọwọ́ nile ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ọwọ́ ti College of Vocation Science and Technology níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí dípúlọ́mà ní ọdún 2012..
wikipedia
yo
Ltdgg Construction and General Services Ltdke Gari and Company níg..
wikipedia
yo
Ltdtel View Capital Alliance Ltdbi mega Global Solutions Tdredre Syfẹ́ Gabe..
wikipedia
yo
Ltdfirst Integrated and (stics Services Tdidiṣẹ rẹ̀ Mala buni bẹrẹ iṣelu rẹ̀ ní ọdún 1992 nígbà tí díje dupo lábẹ́ abúrada ẹgbẹ́ òsèlú National Republican Convention (NRC) láti sojú fún ẹkùn buni ní ẹkùn ìjọba ibilẹ Guj Local Government Council..
wikipedia
yo
O di amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ aṣòfin àgbà ní National Assembly ní ọdún 2000, àti ọdún 2004 tí wọ́n yànan gẹ́gẹ́ bí adarí fún ìgbìmọ̀ University of Uyo..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2006, wọ́n dìbò yànan gẹ́gẹ́ bi alága Advanced Congress of Democrats ní ní IpinleYobe..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007, wọ́n darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ Action Congress látinú ẹgbẹ́ ìṣèlú Advanced Congress of Democrats kí ẹgbẹ́ Action Congress lè fẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin..
wikipedia
yo
Wọ́n yanan láìfọ̀tápè gẹ́gẹ́ bí alága ẹgbẹ́ ìṣèlú tuntun náà Action Congress Party tí wọ́n sì dìbò yáwọ́n ẹgẹ́ bí Alága gbogbo gbọ́ láti ọdún 2007 sí 2010..
wikipedia
yo
buni darapo mo egbe iselu all Nigeria Peoples Party (ANPP) ni odun 2011 ni Ipinle Yobe ti won si yanan gege bi olùbádámọ̀ràn pataki si Gomina Ipinle Yobe Ibrahim Gidam lori eto iselu ati isofin..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2013, tí wọ́n dá àwọn ẹgbẹ́ ìṣèlú papọ̀ láti dá ẹgbẹ́ ìṣèlú All Progressives Congress (APC), wọ́n fi Mai málà buni se akọ̀wé ẹgbẹ́ ohun ní Ìpínlẹ̀ Yobe tí wọ́n sì padà yànan gẹ́gẹ́ bí alága agbá ẹgbẹ́ ohun ní ìpínlẹ̀ Yobe.Mai Mala buni di akọ̀wé àgbà fún ẹgbẹ́ ìgún APC tí wọ́n dìbò yàn án fún ẹgbẹ́ ìgbe ìkàn náà ní ọdún 2014..
wikipedia
yo
lásìkò tí n ṣiṣẹ́ bí Akọ̀wé àgbà yí ni wọ́n dìbò yan Muhammadu Buhari gẹ́gẹ́ ààrẹ Nàìjíríà ní ọdún 2015..
wikipedia
yo
Látàrí ìfarajìn rẹ̀ fún ẹgbẹ́ ni wọ́n tún ṣe yànan sípò akọ̀wé àgbà ẹgbẹ́ ìṣèlú náà lẹ́ẹ̀kejì ní ọdún 2018.Pẹ̀lú ipò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé àgbà ẹgbẹ́ ìṣèlú APC àti Alága ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ Nigeria Shippers Council, wọ́n yànan kí ó wá ṣe adíje dupò gómìnà ní ìpínlẹ̀ Yobe lábẹ́ ẹgbẹ́ ìṣèlú APC ní ọdún 2019.Nínú ìdìbò gbogbo gbo ọdún 2019, wọ́n dìbò yàn án gẹ́gẹ́ bí Gómìnà kẹrin ní ìpínlẹ̀ náà lẹ́ni tí ó jáwé olúborí pẹ̀lú ìbò tí ó tó ẹgbẹ̀rún Ménì àti Olélé mẹ́rin àti mẹ́tàlá nígbà tí alátakò rẹ̀ láti inú ẹgbẹ́ òṣèlú PDP Alhaji Bello ìfòyà ní ìbò ẹgbẹ̀rún Márúnjọ àti 73 ìbò péré.Wọ́n tú ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ ìṣèlú APC ká ní inú oṣù kẹfà ọdún 2020, àmọ́ nígbà tí wọn yóò tún tọ, Mai màlá bú wọ́n fi ṣe ṣe alága àgbà yányán fún ẹgbẹ́ òṣèlú náà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
buni si ni ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ ṣe àpérò gbogbo gbọ́ fún ẹgbẹ́ náà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe yí ni wọ́n mójú tó ìgbòkègbodò ẹgbẹ́ náà fún odidi oṣù mẹ́fà ṣáájú kí wọ́n tó ṣe àpérò gbogbo gbọ́ ohun..
wikipedia
yo
Bákan náà ni a ó gbìyànjú láti kọ́ àwọn iyàrá ìgbékọ́ tuntun, a ó gba àwọn olùkọ́ tuntun tó dáńtọ́, tí a ó sì pèsè àwọn ohun amáyédẹrùn fún àwọn olùkọ́..
wikipedia
yo
Bákan náà ni a ó pèsè ohun ìgbékọ́ tí yóò mú ẹ̀kọ́ rọrùn fún àwọn olùkọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ láti lè fakọyọ bíi tàwọn akẹgbẹ́ wọn lágbàáyé..
wikipedia
yo
Bákan náà ni a ó ti ṣe nílé ẹ̀kọ́ gíga gbogbo..
wikipedia
yo
A rí wípé ètò ẹ̀kọ́ fanimọ́ra, wuyì kí ó lè siṣẹ́ tí a rán..
wikipedia
yo
Sísan owó ìdánwò àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yóò tẹ̀ síwájú bíi ti àtẹ̀yìnwá kí àwọn òbí àti alágbàtọ́ lè nífèbalẹ̀ lórí ọ̀wọ́ ẹ̀kọ́ ṣíṣàn ní ìpínlẹ̀ Yobe..
wikipedia
yo
Láti lè rí wípé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà fọkàn sí ẹ̀kọ́ wọn, a ó bá ìjọba àpapọ̀ ní ìbáṣepọ̀ ta pinminrin lórí fífún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní oúnjẹ nílé ẹ̀kọ́ wa gbogbo..
wikipedia
yo
“Lábẹ́ ìṣàkóso buni, ìjọba rẹ̀ ti na ọwọ́ tí ó tó 2.1 Billion títí di Oṣù Kẹrin Ọdún 2020 láti fi kọ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìgbàlódé méje ní àwọn agbègbè orírírí ní Ìpínlẹ̀ Yobe..
wikipedia
yo
àtojú igbese yi ni lati di àpọ̀jù akeko ku ninu awon ile-eko won gbogbo.IpinleIpinle Yobe wa lara awon ipinle ti awon agbesùnmọ̀mí Boko Haram ti ṣọṣẹ́ julo..
wikipedia
yo
Gomina Mai person buni ti dá àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ ogúnléndé tí wọ́n gbé ní ago ogúnléndé padà sílé wọn tí ó sì tún fi àwọn ohun amáyédẹrùn pẹ́pẹ̀pẹ́ ràn wọ́n lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Ìjọba ìpínlẹ̀ náà pẹ̀lú ìbáṣepọ̀ ilé ìfowó-pamọ́ onídàgbà-sókè African Development Bank lábẹ́ Agro-Proces, Ejibitidvity Encement, and Liagba improvement support, Appeals, Project ni wọ́n ti ṣe ìrànwọ́ fún àwọn ènìyàn náà ti wọ do ẹgbẹ̀rún márùún níye..
wikipedia
yo
ìjọba rẹ̀ náà tún kọ ilégbèé fún àwọn ogúnléndé ní inú oṣù kẹ́sà ọdún 2020..
wikipedia
yo
Iṣẹ akanṣe yi ni Ile-iṣẹ Idape Nigerian National Petroleum Corporation (NDPC), Shell Petroleum Development Company of Nigeria Limited (SPDC) Adech venture (JTV), Shell Nigeria Ìmọ̀bíà and Production Company Limited (MOCp) ati Total Nigeria PLC..
wikipedia
yo
Ṣe agbátẹrù rẹ̀ pẹ̀lú àjọṣepọ̀ ìjọba ìpínlẹ̀ Yobe ní agbami ti ètò ìlera, ìjọba rẹ̀ ti kọ́ ilé-ìwòsàn tí ó ní ilé àyẹ̀wò kanọ̀ nínú Ọgbàlẹléméjì tí ó ṣèlérí rẹ̀ fún ará ìlú, àwọn ilé-ìwòsàn náà ni wọn yóò ma ṣe àyẹ̀wò fún àwọn aláìsàn tí wọn yóò sì ma fún wọn ní oògùn lọ́fẹ̀, ó tún kọ́ ilé ìgbẹ́ fún àwọn takọ-tabo oníṣẹ́ ìlera nínú àwọn ilé-ìwòsàn yí gbogbo kí wọ́n lè má tọ́jú àwọn ènìyàn nígbà gbogbo tí wọ́n bá yọjú.Lágbọ̀nrínrin ti ilégbèé, ìjọba rẹ̀ ti kọ́ ilé tí ó ẹgbẹ̀rún kan ó lé lọ́gọ́jọ láàrin ọdún méjì àkọ́kọ́ tí ó gbàṣẹjọba..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó tún fẹ́ ṣe nínu apákejì ìṣèjọba rẹ̀.Ẹ lè woìpínlẹ̀ Yobegovernors of Yobe Statelist of Regbe in Yobe Statelist of State Governo of Nidele'ani Governo' Forumàwọn Àmì-ẹ̀yẹ Ìran gba ami-ẹ̀yẹ Ìdánilodínlógójì ti Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà ìyẹn ìyẹn commander of the Order of the Niger (Con) ní inú osu Kẹwàá ọdún 2022 láti ọwọ́ Ààrẹ Ana Muhammadu Buhari.Àwọn ìtọ́kasí Living People Births Birth from from 2008 All Progressives Congress Poliss of Leeds Bec University— of Yobe State.. State..
wikipedia
yo
Umo Bassey Eno tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Kẹrìnlélógún Oṣù Kẹrin Ọdún 1964, jẹ́ Olùṣọ́ Àgùtàn Ilé-ijọsin All Christain Minitary International àti olóṣèlú tí ó tún jẹ́ Gómìnà ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom nínú ìdìbò tó wáyé ní ọdún 2023., ó sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
òun ni Kọmíṣánà tẹ́lẹ̀ rí fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ àti omi àlùmọ́nì fún ìpínlẹ̀ Akwa Ibom.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹrin ọdún 1964, ní ìlú rẹ̀ IKOT EKPENE Ìró tí ó wà ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ₦sit-nnì71..
wikipedia
yo
O lọ si ile-eko alakoobere local authority Primary School ti o wa ni ipinle Eko, nibi ti o ti gba iwe eri eko akobere he attended local authority Primary School in Lagos State, where he got his first school leaving Certificate..
wikipedia
yo
Francis tí ó wà ní ìlú Eät tí ó sì parí ìpele Èkó yí ní Vilẹ́nuey High School tí ó wà ní Ikeja ní Ìpínlẹ̀ Èkó ..
wikipedia
yo
Ó gba ìwé-ẹ̀rí ẹ̀kọ́ àgbà jáde nínú ìmọ̀ ìbáṣepọ̀ àwùjọ ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì UYÓ tí ó sì gba ìwé ẹ̀rí Masters jáde nínú ẹ̀ka ìmọ̀ yí kan náà.Ìṣeǹṣe rẹ̀wọ́n gbáà ṣíṣe ní ilé-iṣẹ́ Union Bank lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndírì rẹ̀ sáájú kí ó tó lọ ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ dáhùngbè Machine Ìsíls Nigeria Limited àti Norman Holdings Limited, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà ṣáájú kí ó tó lọ dá ilé-iṣẹ́ Royalty Group tí ó jẹ́ olùdásílẹ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n yànan sí ipò Komisana fún ọrọ̀ ilẹ̀ àti omi àlúmọ́nì ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní ọdún 2021 lábẹ́ Gómìnà Údom Emmanuel ó kọ̀wé dupò náà sílẹ̀ láti díje du ipò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ náà ní ọdún 2023.Àwọn Ìtọ́kasí1964 BirthsPeople From Akwa Ibom Stataving Popde Nivlope-Century Nigerian Polisped Democratic Party State Governo Of Nigeriagovernors of Akwa Ibom State..
wikipedia
yo
Andrés Iniẹ Lujan (ti a bi ni ojo Kọkànlá osu karun-un ọdun 1984) je agbaboolu omo orile ede Spain..
wikipedia
yo
Ó wà lára àwọn tí ọ̀pọ̀ ká sí agbábọ́ọ̀lù àárín tí ó dá jù ní àgbáyé..
wikipedia
yo
Astaẹ lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù ní Barcelona, ní ibi tí ó ti jẹ́ adarí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù náà fún sáà mẹ́ta..
wikipedia
yo
Astaẹ ran orílẹ̀ èdè Spain lọ́wọ́ láti jáwé olúborí nínú UEFA Euro 2008..
wikipedia
yo
Iniẹ tun agbabọọlu gboogi ti o ran ẹgbẹ agbabọọlu Spain lati jawe olubori ninu 2010 FIFA World Cup.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Andrea Pirlo (ti a bi ni ojo kokandinlogun 1979) je agbaboolu omo orile ede Italy ti o je Olutoni agba egbe agbaboolu Serie B sampdoria..
wikipedia
yo
O wa lara awon ti opolopo ka si agbaboolu ipo aarin ti o da julo.Kabelo bere si n gba boolu fun egbe Brescia ni odun 1995, o jawe olubori bori Serie B ni odun 1997..
wikipedia
yo
O fowo síwe fun ẹgbẹ agbabọọlu Serie A ti Inter Milan leyin ọdun kan, ṣugbọn o pada lọ si ẹgbẹ AC Milan ni ọdun 2001..
wikipedia
yo
Ni ẹgbẹ agbabọọlu naa ni pirlo ti di ogboonrìgì agbabọọlu, o jawe olubori ninu ipo Serie A meji, UEFA Champions League meji, UEFA Super Cup meji, FIFA Club World Cup meji, Coppappa Italia meji, ati Supercoppa Ogunlo Kan.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Thomas Stanley Holland (tí a bí ní ọjọ́ Kínní Oṣù Kẹfà Ọdún 1996) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain..
wikipedia
yo
Ara awon ami eye re ni British Academy Film Award ati Saturn Awards meta..
wikipedia
yo
Àwọn àtẹ̀jáde míràn ti pèé ní òṣèré tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní ìrán rẹ̀.Holland jẹ́ ọmọ ọdún mẹsan-an nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe, ó darapọ̀ mọ́ ẹ̀kọ́ ijó kan nígbà náà, ọ̀kan lára àwọn oníjó sí Kíyèsi, èyí mú kí ó ran lọ́wọ́ láti fi ìfẹ́ hàn sí jíjẹ́ ará àwọn òṣèré nínu eré Billy Elliot The Musical ní Victoria Palace Theatre..
wikipedia
yo
Holland bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣeré ní péré wú nígbà tí ó ṣeré nínú fíìmù The impossible (2012) gẹ́gẹ́ bí ọ̀dọ́kùnrin tí ó sọnù sínú Tsùnámì..
wikipedia
yo
Thomas William Hiddneton (tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kejì ọdún 1981) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain..
wikipedia
yo
Scott FitzGerald nínu fíìmù Net Allen tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Lomas in Paris, àti eré Steven Spielberg tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ War Horse..
wikipedia
yo
Ní ọdún kan náà, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Empire Award for Best Malé Newco..
wikipedia
yo
Awon ere miran ti o ti kopa ni M Terence Davies' The deep Blue Sea (2012), Jim Jarmus's romantic Vamire Film Only Lovers Left alive (2013) ati Guillermo del Toro's Crison Kole (2015).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Samuel Leroy Jackson (ti a bi ni ọjọ kokanlelogun osu kejila odun 1948) je osere omo orile-ede Actor Amẹrika..
wikipedia
yo
O jẹ okan lara awon osere ti o gbajumo julo ni iran re a, awon fiimu ti o ti sere ti pa iye owo ti o le ni bilionu metadinlogun dola ($27 billion), eyi mu ki o je osere keji ti awon ere re ti pa owo ju...
wikipedia
yo
Ní ọdún 2022, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Honorary Award.Jackson bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré pẹrẹwu ní ọdún 1980 nígbà tí ó ṣeré nínú Mother courage and Her Children ní The Public Theatre..
wikipedia
yo
Laarin odun 1981 si odun 1983, o ṣere a soldier's play off-Broadway..
wikipedia
yo
O tun ṣere ninu fiimu The Piano Lesson ni odun 1987 ni Yale Repertory Theatre..
wikipedia
yo
Awọn ere ti Jackson kọkọ ṣe ni Coming to America (1988), juice (1992), True Romance (1993), Menace II Society (1993), ati Fresh (1994).Awọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
}} ayọ Chess jẹ́ ayò tí a ma ń tà lórí tábìlì lábẹ́lẹ̀ láàrín onta ènìyàn méjì..
wikipedia
yo
ọ̀ntà kọ̀ọ̀kan ni wọ́n má dá ayọ̀ wọn mọ̀ pẹ̀lú kí ìkan apá ilẹ̀ kan dúdú kí ìkejì sì funfun..
wikipedia
yo
Àwọn Onta wọnyi ni wọn yóo ma dari àwọn ayọ̀ tí wọ́n jẹ́ ikọ̀ ọmọ ogun ilé kọ̀ọ̀kan tí wọ́n ń pè ní Chess pieces..
wikipedia
yo
Gbogbo ète ati èrò ọnta kọ̀ọ̀kan ni kí o fi ikọ̀ ọmọ ogun ayọ̀ tìrẹ pa ẹnìkejì rẹ láyọ̀ tí wọn ń pè ní Checkmate..
wikipedia
yo
Ṣáájú kí èyí tó wáyé, wọ́n gbọdọ̀ dé tàbí pa ọba tí ó jẹ́ olórí..
wikipedia
yo