cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ìjàpá ni àrùn ló fà ó! Àrùn ọ̀hún sì wà ní ìdí gbogbo ẹranko, àwọn tí ó bá ti yọ tí wọ́n ní wọ́n ń tóbi bíi erin, ẹfọ̀n, ìgalà, ati bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ, ní ìdí èyí, àdán ati ìjàpá yóo bá ara wọn yọ àrùn náà..
wikipedia
yo
Inú àdán dun o ṣi ìmọ́nran ti ìjàpá mu wa yìí, kò tilẹ̀ yiri rẹ̀ wo tí ó fi gbá a..
wikipedia
yo
Ìjàpá rèé, igbà ti ó wà ni idi rẹ, ti o bá fi mu nkan, kò si ẹni ti o lè fà á yọ..
wikipedia
yo
Kéré ti àdán ti ọwọ́ bo ìdí rẹ̀ ni ó fi igba idì rẹ̀ mú síkùn, àdán fa ọwọ́ rẹ yó ti ni ìdí ìjàpá..
wikipedia
yo
Ó kígbe títí ṣùgbọ́n ìjàpá kò sí ìdí rẹ̀ débi pé àdán yóò rí ọwọ́ rẹ̀ yọ padà..
wikipedia
yo
Ìjàpá bá ṣe ojú paìkó ló sọ fún àdán pé tí kò bá gbe oun padà sí ilẹ̀ òun ní ìsàlẹ̀, á jẹ́ wípé ọwọ́ àdán gé dànù nùú..
wikipedia
yo
Báyĩ ni ó di dandan kí àdán gbé ìjàpá padà sí ilé rẹ̀ ní ìsàlẹ̀ igi láti ilé àdán tí ó wà lórí igi.Ẹ̀kọ́ inú ààlọ́ kí a má máa gba oró láì kọ́kọ́ yẹ̀ wò tí òhun ènìyàn kan bá dùn mọ̀nrànǹmọnran kí a máa lo ọgbọ́n inú wa kí a ṣọ́ra fún ọ̀rẹ́ tí ìwàǹwára rẹ̀ bá ti pọ̀ jùàwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Nicole Evanlineline Lilly (tí a bí ní ọjọ́ kẹta Oṣù Kẹjọ Ọdún 1979) jẹ́ òṣèrébìnrin àti ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè Kánádà..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ nígbà tí ó kó ipa Kate Austen nínu eré tí àpéle rẹ̀ jẹ́ lost (2004–2010), òun sì ló jẹ́ kí wọ́n yàn fún àmì-ẹ̀yẹ Golden Globe Award for Best Actress in a Drama series..
wikipedia
yo
Lily ti kopa ninu ọpọlọpọ fiimu bi The hurt Locker (2008), Real Steel (2011), gege bi tauriel ninu awon fiimu The hobbít, ninu The Defohùn of SMugh (2013) ati The Battle of the Five Armies (2014)..
wikipedia
yo
O ko ipa Hope Van Dyne ninu fiimu Marvel Cinematic Universe tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Ant-man (2015)..
wikipedia
yo
Lilly tun jẹ onkọwe iwe awọn ọmọde ti àpèlé rẹ jẹ The Squickerwonkers.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Tessa Lynne Thompson (tí a bí ní Ọjọ́ Kẹta Oṣù Kesan-an Ọdún 1983) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré pẹ̀lú ilé iṣẹ́ Los Angeles Women's Shakespeare nígbà tí ó ń kàwé ní ilé ìwé Santa Monica College..
wikipedia
yo
Ó wà nínú eré The Teúabẹ́rẹ́ àti Romeo and Juliet, ipa rẹ̀ nínu eré Romeo and Julie sì mú kí wọ́n yàn fún àmì-ẹ̀yẹ NAACP Theatre Award..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ nígbà tí ó ṣeré nínu fíìmù ti Tina Noury Gujáde; Mississippi Damned (2009) àti fíìmù Tyler Perry tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ for Colored Girls (2010). àwọn eré tí ó kópa nínuàwọn fíìmùàwọn eré tí ó wà ní ìrífíìmù àwọn orinàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Union Bank of Nigeria PLC jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-ìfowópamọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà, tí Olú-ilé-iṣẹ́ rẹ̀ wà ní Victoria Island, Lagos..
wikipedia
yo
Ó ti ń ṣiṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, láti ọdún 1917.Àkópọ̀ Union Bank jẹ́ ilé-ìfowópamọ́ nlá, tó ń ṣiṣẹ́ fún àwọn ènìyàn, ilé-iṣẹ́ kékeré àti alábọ́dé, pẹ̀lú àwọn ilé-iṣẹ́ ńlá..
wikipedia
yo
Ní oṣù keje ọdún 2009, wọ́n tò ó pọ̀ sí ipò 556th, ìyẹn mọ́ àwọn ilé-ìfowópamọ́ tó tóbi jù lọ ní àgbáyé, àti sí ipò kẹrìnlá, ìyẹn sára àwọn ilé-ìfowópamọ́ tó tóbi jù lọ ní ilẹ̀ Africa..
wikipedia
yo
Titi di ojo kokanlelogbon osu keta, odun 2018, gbogbo dúkìá ile-ifowopamọ naa n lo bi i ngN1,381 yinbonófóònù (US$ 4.1billion)..
wikipedia
yo
Owó tí ó kan àwọn tí ọ̀rọ̀ kan nínúh ilé-ìfowópamọ́ náà ń lo ngn286 bíóófóònù (US$ 851 million).Ìtàn a lè tọ́ka ìtàn ilé-ìfowópamọ́ yìí sí ọdún 1836 nígbà tí àwọn òṣìṣẹ́ báńkì ìlú London àti oníṣòwò ilẹ̀l Britani gba ìwé Ẹae Ọlọ́lá Lárùti Owó Wid IV láti máa ṣàkóso ètò Ìṣòwò Báǹkì ní Caribbean..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ Àwọn Alagun yìí sí Ṣẹ̀dá Mísede Bank.Látàrí òfin tí Iléìgbìmọ̀ aṣòfin gbé kalẹ̀l pé àwọn ilé-ìfowó lé ń ẹ̀ka ilé-iṣẹ́ káàkiri Caribbean àti lẹ́yìn odi, kọsils Bank wá bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ní ọdún 1917..
wikipedia
yo
Iṣẹ naa bẹrẹ pẹlu dida ile-iṣẹ si Ipinle Eko, Jọ ati Port Harcourt..
wikipedia
yo
Wọ́n sí àwọn ẹ̀ka mìíràn sílẹ̀, ní ọdún 1918, ní Ebute Metta, Onitsha, Ìbàdàn, Kano, àti Zaria, wọ́n sì tún dá omitan sílẹ̀ ní burutu, ní ọdún 1921.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Florence kasumba (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹwàá ọdún 1976) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Uganda àti Jámínì..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún ṣíṣe eré nínu àwọn fíìmù Jamani àti Dutch..
wikipedia
yo
O tun ko ipa gege bi Senator lọ́rọ̀tha ninu wonder Woman (2017), Shenzi ninu The Lion King (2019), ati Skoko Witch of the East ninu fiimu NBC tí àpéle rẹ jẹ́ Emerald City (2017).ipilẹ won bi Florence Kasumba ni ọjọ kerindinlogun Oṣu Kẹwàá odun 1976 ni Kampala, orile ede Uganda..
wikipedia
yo
Wọn to dagba ni ESsen, Germany, nibi ti o ti lo ile iwe alakobere ati ile iwe sekondiri..
wikipedia
yo
Ó padà gba àmì-ẹ̀yẹ ẹ̀kọ́ nínú eré ṣíṣe, orin kíkọ àti ìfà jíjó ní fọ́nDoku University of Applied Sciences ti Tilburg, Netherlands..
wikipedia
yo
O n gbe ni Berlin, orílẹ̀ èdè Germany.àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
pamọn Bank, ti a tun mọ si pamọati Bank Plc., jẹ ọkan lara awọn ile-ifowopamọ ni orilẹ-ede Naijiria, ti olu ile-iṣẹ wọn wa ni Victoria Island, Lagos..
wikipedia
yo
O jẹ ile-ifowopamọ to ti gbàwẹ̀ aṣẹ, ti Central Bank of Nigeria si ti fòntẹ̀ lu gẹ́gẹ́ bí banki oníṣòwo.Ile-ifowopamọ ti parẹ́ ti Pékà láti ibi gegele, ó sì ti di ile-ifowopamọ to duro ṣinṣin, tó sì ti gbayi láwùjọ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2005, ilé-ìfowópamọ́ yìí gbà Fá International Bank PLC ("FAF") àti Manny Bank PLC ("manny") láti ṣẹ̀dá ọ̀kan nínú àwọn àwọn ìrún mẹ́wàá tó ga jù lọ ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2011, banki naa wa ni ipo keje ninu ààtò awọn banki to tobi ju lọ ni Naijiria, ati ipo karundinlogbon ninu ààtò awọn banki to tobi ju lọ ni Africa..
wikipedia
yo
Wọ́n tún fi ìyọpọ̀ kérin, ìyẹn lára àwọn banki tó dara jù lọ ní orílẹ̀-èdè Nàíjíríà.ìtàn yìí Bank of Nigeria fíkọ́ sílẹ̀ ní ọdún 1987, wọ́n sí bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọdún 1988..
wikipedia
yo
Ni ibẹrẹṣe, won bẹrẹ pẹlu owo kékèèké.025 Bank yi pada lati di ile-ifowopamọ, onisowo nla ni odun 1999, pelu igbiyanju lati dagba gege bii ile-ise to ni ipin ikoko amo o di ile-ise to nipi gbangba ni odun 1999 bakan naa..
wikipedia
yo
Ọdún náà lórúkọ rẹ̀ sí yí padà sí nílẹ̀áti Bank PLC.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Polaris Bank limited jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-ìfowópamọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O gba iwe-aṣẹ lọwọ Central Bank of Nigeria, eyi to je oluṣakoso àwọn ile-ifowopamọ ni orilẹ-ede naa..
wikipedia
yo
ní oṣù Kẹwàá ọdún 2022, strategic Capital Investment Limited (s80) gba banki yìí, láti sọ ọ́ di ohun ìní wọn.Awopọ̀ Polaris Bank jẹ́ olùpèsè ètò ìṣúná nla ní apá ìwọ̀òrùn Afirika àti Central Africa pẹ̀lú Olú-ilé-iṣẹ́ ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1990, banki naa gba iwe-aṣẹ lati maa ṣòwò kékèèké..
wikipedia
yo
Lọ́dún kan náà, ó yí orúkọ dá sí Prudent merchant Bank limited..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2006, Prudent Merchant Bank limited parapọ̀ mọ́ báńkì meri mìíràn láti di skye Bank PLC.
wikipedia
yo
ReliAnce Bank limited co-Ọ̀perative Bank PLC.Ní oṣù karun-un ọdún 2021, báńkì náà ṣe ìfilọ́lẹ̀ vulte, èyí tó jẹ́ pẹpẹ ilé-ìfowópamọ́ náà lórí ẹ̀rọ-ayélujára..
wikipedia
yo
Ile-ifowopamọ naa ni ipese fun Iṣowo lori ẹrọ-ayelujara ati lori ẹrọ-ìbánisọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ilé-ìfowópamọ́ náà gba MainStreet Bank Limited.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Adetunji Femi Fade ni Alaga ẹgbẹ́ Tourism Praciers of Nigeria (AT1950), eyi to wa ni apa ìwọ̀-oorun ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun si ni adari agba ti ile-iṣẹ jethro Tours and Awori Initiative, o si tun je ọmọ ẹgbẹ trade promotion Board fun ẹka to n ri si eto iṣowo ati ile-iṣẹ ni ipinlẹ Eko.eto Eko ile-iwe Loyola College ni Ibadan ni o ti pari ẹkọ girama, ni ọdun 1980..
wikipedia
yo
O si tẹsiwaju lati kẹkọọ gboye ninu imọ Business Administration and Management ni Samford University, lati ọdun 1981 wo ọdun 1984.Iṣẹ rẹ Adetunji ni oludasile Awori Tourism Buand Firm, ati Aare Association of Tourism Practitioners in Nigeria, eyi to je ẹgbẹ to n ri si ọrọ irin-ajo ati igbega ati iduroṣinṣin awọn ile-iṣẹ to n ri si eto Irin-ajo..
wikipedia
yo
Oun naa si ni oludari agba ati oludasile ile-iṣẹ dinat ọmọtí Inc..
wikipedia
yo
Adetunji ti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìrírí nínú iṣẹ́ tó ń rí sí ètò ìrìn-àjò, èyí sì hàndé nínú ìṣẹ̀dásílẹ̀ ẹgbẹ́ kan tó sọ ní Jethro Tours Institute.Ní ọdún 2019, Ẹ̀ka tó ń rí sí ọ̀rọ̀ àṣà àti ìrìn-àjò ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, pé Adetunji láti wá sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ ọdọọdún wọn láti Sgbẹ̀lárugẹ Àṣà àti ètò ìrìn-àjò tó máa ń wáyé ní ìlú Abeokuta.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ajegunle ti Ee tun n dada ni "àj City" Or simply "àj", je agbegbe kan ni ipinle Eko ti o wa ni abe ijoba ibile Jèhófàrọ̀mí Ifelodun.Ajegunle pààlà pelu ibudo etikun Apapa wharf ati ipinlecan tin, ti won je ibudo ìkẹ́rù wọle lori omi ti o toni julọ ni ipinle Eko ti oriṣiriṣi nkan ti wọ orilẹ-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Iye àwọn plugbé Ajegunle jẹ́ ẹgbẹ̀tàléláàádọ́ta ènìyàn níbi tí a ti rí gbogbo ẹ̀yà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn tí wọ́n jẹ́ olùgbé tí wọ́n pọ̀ jùlọ ní agbègbè náà ní àwọn ẹ̀yà Yorùbá tí wọ́n jẹ́ Ijaw àti Ìlàjẹ.Àwọn lààmì-laaka ènìyàn ìbẹ̀oríṣiríṣi àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ lààmì-laaka ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti gbogbo àgbáyé ni wọ́n tara Ajegunle dìde..
wikipedia
yo
Lara won ni a ti ri agbaboolu tẹlẹri fun orile-ede Naijiria ti o tun ti je akonimọọgba un orile-edeNaijiria ri Samson siàsíá..
wikipedia
yo
Bakan naa ni a tun ti ri agbabọọlu atamatase ti o n gba bọọlu lowo iwaju fun iko Manchester United, iyẹn Odion Ẹ̀tọ́Halo., Ibe naa ni a tun ti ri agbabọọlu lowo eyin fun iko agbabọọlu orile-ede Naijiria tẹlẹ ri, iyẹn taribo West..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni a rí Chinwendu Ihezuo tí ó gbá bọ́ọ̀lù jẹun nínú ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù obìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
A tun ri Emmanuel Amọyìèké, ti oun naa jẹ agbabọọlu fun orilẹ-ede Naijiria tẹlẹ..
wikipedia
yo
Lára won naa ni ìlúmọ̀ọ́ká olórin Takasufe táà showkey.Àwọn ìtọ́kasí Jopernn)". of Lsssslums in Nigeria..
wikipedia
yo
Àwórì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà àwọn ọmọ Yorùbá ti ń sọ èdè kan patò, èyí ti i se ede Yoruba.ìwọ̀n agbègbè ni ibamu pẹ̀lú àṣà, àwọn ẹ̀yà àwórìà wa ni ìpínlẹ̀ Ogun ati Ìpínlẹ̀ Èkó, ní orílẹ̀-èdè Naijiria àwọn ìlú bíi Ikorodu, Epe, Badagry, ọ̀ĺl, Ado-Odo, Ikarun-I, Iroko, Agbarabi, Àka, àti ti Ibùgbé àwọn Àwóri, láàárín Ìpínlẹ̀ Ògùn, ti wọ́n dá ní ọdún 1976, ní ọdún 1976-ede Naijiria. ní ará-ede Olodumare ni itan-akọọlẹ ni itan-akọọlẹ nipa aarin sí aarin, èyí tó bẹ̀rẹ̀ ìjọba sin ìjọba sin ìjọba sin ìjọba sin ni ìtàn ni agbo kẹrin.. Àwọn ègbe, ní gbogbo ọmọ kan ni àgbe gbogbo ọmọ , ní ìpínlẹ̀ Ògùn, ti ń dá pẹ̀lú ọdún rẹ̀, ní agbo Ògùn-ede Irùn mọ́ èdè Nàìjíríà, ní ọdún rẹ̀- ] Àwọn gbé àwọn àjàga, ní ìpínl ogun , ti àja mọ́ 1976, ní ọdún Nàìjíríà, ati àja àwọn ti - ẹ̀kan ni ìtàn. ti àgbe mọ́ sí gbogbo omi, ni ìpín gbogbo ti ìpínlẹ̀ Èkó, ní ìtàn-èdè Nàìjíríà ni àjásin àwọn ìlú gbogbo (itan, ele ni agbo àrìèko sí ìdánu gbogbo àwọn tí ati àgbe irin ti ń sọ ọmọ kan ni ọmọ ogun * ni ọdún rẹ̀. Àwọn ti orílẹ̀ èdè rẹ̀. Àwọn ará àgbèlà-ìkan ni ìpínlẹ̀ ogun ati ìpín Èkó, ni orílẹ̀ Ògùn ni ìlú bíi ìjọba , elègun ọ̀gbọ̀adẹ̀ràn dá ni àárín è
wikipedia
yo
Àwọn ni wọ́n dá ìlú Èkó sílẹ̀, wọ́n jẹ́ pẹjapẹja àti oníṣòwò, ó sì fìdí múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí owó tí wọ́n ń ṣe ní apá ìwọ̀òrùn Áfíríkà.Ìtàn orísun ìtàn náà ni pé, Olófin àti àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ kúrò ní ààfin Ọba Odùduwà (tó jẹ́ Olùṣẹ̀dásilẹ̀ ilẹ̀ Yorùbá) ní Ilé-Ifẹ̀, wọ́n sì ṣí lọ síhà Gúúsù létí odò kan..
wikipedia
yo
Odùduwà ti fún Ọlọ́fin ní àwo kan tí wọ́n mọ́, ó ní kí ó gbé e sórí omi, kí ó tẹ̀lé e títí tí ó fi máa rì sínú odò.Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́ tí wọ́n kúrò ní Ilé-Ifẹ̀, àwo náà dúró lójijì sí agbègbè olókèmejì, nítòsí Abeokuta tòde òní..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́tàdínlógún, ó tún bẹ̀rẹ̀ sí í lọ, ó sì dúró sí Òkè-Ata fún ọjọ́ mẹ́tàdínlógún mìíràn..
wikipedia
yo
Ní ìparí ọjọ́ mẹ́tàdínlógún, àwo náà tún bẹ̀rẹ̀ síí lọ, ṣàdédé ni ó dúró sí ìhà gúúsù ti Abẹ́òkúta lónìí, níbi tó ti dúró fún ọjọ́ metdínlógún mìíràn..
wikipedia
yo
Níbi yìí ni àwọn ọmọ Olófìn kan pinnu láti dúró, tí ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Osho Aro-bí-ológbò-ẹgàn sì jẹ́ olórí..
wikipedia
yo
àwo náà tẹ̀síwájú sí ìsàlẹ̀, ó sì tún dúró ní Isi..
wikipedia
yo
Ọlọ́fin bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ pé kí wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í dá àwọn ìletò kan sílẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọlẹ́yìn náà sì béèrè pé “Níbo ni àwo náà wà?”, Ó sì dáhùn pé “Awo ti rí”
wikipedia
yo
Olofin ni iyawo meji, orukọ wọn si ni Akesan ati Ajaiye..
wikipedia
yo
Ake bímọ okùnrin méjì (ìyẹn Ogunneneru àti Ogunyíyí), tí AjaIye sí Yún..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí wọ́n tẹ̀dó sí ìlú Iserí, Ọlọ́fin lọ wádìí ọ̀rọ̀-onífẹ̀ẹ́ Ifá níbi tí wọ́n ti ní kí wọ́n lọ síbi tí omi Iyọ̀ wà..
wikipedia
yo
Wọ́n sì ṣí kúrò ní ìṣeri, tí wọ́n wá lọ sí Iddo, níbi tí wọ́n sì gbé..
wikipedia
yo
AjáIye bí ọmọ mẹ́jọ lẹ́yìn-ó-rẹ̀yìn, tí wọ́n sì máa dàgbà di idẹjọ òde-òní..
wikipedia
yo
Wọ́n sì máa ń ṣayẹyẹ àwọn ọdún ẹ̀sìn mìíràn, bíi ẹ̀sìn Mùsùlùmí àti ọdún Kérésìmesì fún àwọn Kirisiteẹni..
wikipedia
yo
Èyí sì máa ń mú kí àwọn ọmọ-ìlú tó wà nílẹ̀ òkèèrè padà wálé láti wá bá wọn sàjọyọ̀.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Articles with Hcards Komegne jẹ́ ayàwòrán tí ó kalẹ̀ sí ìlú Douala àti olùpolówó ti ààyè àwòrán àsìkò ní ìlú Kamerun .ẹruìgbésí ayé àti iṣẹ́ Abi koko (Dojúgne ní ọdún 1950 ní Btou ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1956 ó lọ sí Yaoundé níbití ó ti lọ sí ilé-ìwé àti pé ó bẹ̀rẹ̀ ìyàwòrán àti gbígbọ́ gbogbo àwọn orin..
wikipedia
yo
Ní 1960-62 ó ṣe àgbéjáde eré àkọ́kọ́ rẹ̀ Le Boxeur àti ní 1965, lẹ́hìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpèníjà, ó gbé lọ sí Douala níbití ó ti pàdé Jean Bìtíer, Oluyaworan magbowo tí yoo fa u láti kún..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1968 ó jáwé olú bori nínú ìdíje ìyàwòrán Biscuits Berlin àti pé ó ṣiṣẹ́ fún ọdún kan lórí ọkọ̀ ojú-omi kékeré kan tí ó lọ kiri àwọn eti òkun ti arin gbùngbùn Afrika..
wikipedia
yo
Ni 1971 o se alabapin si iṣafihan ẹgbẹ akọkọ rẹ ti a ṣeto ni Douala nipasẹ igbimọ française pour la formation des Cadres..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1972 o si igi kan lẹgbẹẹ ile rẹ nibiti o ti pe awọn akọrin ati nibiti o ti nṣere bi akọrin ati akọrin; ni igba diẹ o di akọrin ti ẹgbẹ orin "agbara awọn alawọ dudu"
wikipedia
yo
Ní ọdún 1990 ó ṣe ìgbeyàwó fún ìgbà kejì àti pé ó ní ọmọbìrin kan fún ẹnití ó ṣe ìyàwá ìfihàn iṣẹ́ rẹ̀ ti àpé ní "Evanescence ní ọdún 2008 ní Esspace Doual'artart..
wikipedia
yo
Lẹhin ikọsilẹ miiran, o ṣe igbeyawo fun igba kẹta o si ni ọmọ mẹrin..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1997 o jẹ ipalara ijamba kan ati pe o wa ni ile-iwosan fun osu mẹrin..
wikipedia
yo
Ni 2000 o ni lati lọ kuro ni Atelier rẹ ni agbegbe Bonadibo ni Douala ati pe o lọ si CCCC agbegbe.Lẹhin ifọwọsi awọn aworan rẹ "Ggigne Gaston", "koko decor", "Gaston Kome", o yan lati maa fọwọsi awọn aworan rẹ pẹlu orukọ koko Komegne, apapọ orukọ baba rẹ (Koulejo) ati orukọ rẹ (Gugne)..)..
wikipedia
yo
Ninu iṣẹ́ ti ara ẹni, ó sọjúmọ́ lórí orin, ijó, àwọn panṣaga, òṣì, ìgbésí ayé àlè ati àwọn ìbòjú Ìparadà..
wikipedia
yo
Ni 1974 o se agbejade aworan ti fiimu Poísún Poísún nipasẹ Daniel Kamga, fiimu akọkọ ti Ilu Kamẹrika ati ni ọdun 1976 o ni iṣafihan adashe akọkọ rẹ ni Quargbé Latin, ẹgbẹ ile ounjẹ kan ni Douala..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1979 ó kópa nínú ìdíje àkọ́kọ́ fún àwọn ọ̀dọ́ olùyàwòrán ọmọ ìlú Kamemex..
wikipedia
yo
Ni 1993 o je oludari ise ona ti Doual'art Pop '93, idanileko ti a ṣeto nipasẹ Doual'art ni agbegbe Madagascar ni Douala ninu eyiti awọn oṣere 25 ṣe awọn Frescos lori awọn ọja ìṣura ti agbala ilẹ kan; ni ọdun kanna o se alabapin ni glutamicJÍSt Exquis ni Mbappé Lep Stadium ni Douala ati pe o jẹ ọmọ Igbimọ ti Festival National des arts et de la Culture..
wikipedia
yo
Ni 1997 o se alabapin ninu le Kwatt, idanileko ti a ṣeto nipasẹ Doual'Art ni agbegbe Makepe Petit-pays ni Douala ati ni 1998 ni entr'artiste Shted nipasẹ Marila borelo ni Doual'art..
wikipedia
yo
Ni 1979 o ṣẹda ẹgbẹ akọkọ ti awọn oṣere ti Cameroon Cercle Maduta ("Megèlèber tumọ si "Awọn aworan" ni ede Douala) pẹlu awọn oṣere viking Kanganyam, Jean-Guy atakoua ati Samuel Abele ..
wikipedia
yo
Buclec Maduta tilẹ̀kùn ni 1983 nigbati koko Komegne ṣe awari pẹlu awọn oṣere miiran CapLit - cercle des artites plastis du littoral ..
wikipedia
yo
Ni 1980 ha ifihan ni Mẹ́nuiserie etd Mucam MeIbùdóru, a aga Itaja; ni 1981 O ni iṣafihan ifẹhinti akọkọ rẹ (1976-1982) ni Ile-iṣẹ Asa Amẹrika ati ni 1982 ni Ile-iṣẹ Asa Faranse ni Yaoundé ..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ ẹgbẹ ti o ṣẹda ni ọdun 1994 ti ẹgbẹ aṣa ti Kheops Club eyiti o ṣajọpọ awọn oṣere ceMRoru!’ mẹwa pẹlu ẹrọ ti igbega iṣẹ ọna wiwo ni Ilu Kamẹrika..
wikipedia
yo
Ni 1995 o se afihan awọn oṣere ọdọ Joel MPAH DAD, Blaise Bang, SaliFou Lindou, Hervé Youmbi ati Hervé yamgu ninu ifihan “tele Ṣósoomi ni Mam Gallery ni Douala..
wikipedia
yo
Ní 2001 ó jẹ́ olùtọ́jú tí ẹgbẹ́ fihàn yànn & Co ni Atelier viking àti ti quatt'art, ìdánile ọ̀sẹ̀ kan àti ìfihàn pẹ̀lú àwọn òṣèré 22 tí ó síì afẹ́fẹ́ ní agbègbè BALI ní Douala..
wikipedia
yo
Ní 2002 ó kópa nínú quatt'Art II ní àgbò Deï ní Douala..
wikipedia
yo
O tun jẹ ọkan ninu awọn ọmọ ẹgbẹ ti o ṣẹda ti aaye aworan ti o nṣiṣẹ olorin-ṣiṣe Art kidinrin .iwe akosile "Revue noire" - Special issue on Cameroon, n..
wikipedia
yo
Tayou, 1997 distributed on the TV Channel "arte" in 1998.
wikipedia
yo
Ko Komegne fètè Qàrànte anrora d'arts plastiques..
wikipedia
yo
Art et transformations urbaInes a Douala /// Art and Urban transformations in Douala..
wikipedia
yo