cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ẹwà wọn sì máa ń jẹyọ nínú àwo tí Olódùmarè nfi a wọ́n lọ́rẹ àtọ̀ ọmú tí ó fi ṣe àfikún ẹwà wọn..
wikipedia
yo
Ọmú tàbí ọyàn obìnrin ni iyì rẹ ọ̀hún sì ni ònọ́n tó ń fa àwọn ọkùnrin tó sì ààbí ẹmu tó ń mú wọn mọ́lẹ̀ lára obìnrin odi méjì, ìjìnlẹ̀ ohun eleu Ifá apá kínní pg 54–1–3 fìdí èyí milẹ̀ pe funfun nìyí ẹ̀yin ẹ̀gún gadáa nìyí ọ̀run ọmú siki siki nìyí Obìnrin obìnrin si tuntun nìyí obìnrin 54 54 1-ohun iyì àti Ámùji ni fún ọkọ rẹ̀ bí ẹ̀yin odi méjì obìnrin bá funfun..
wikipedia
yo
Bákannáà ni ìfà tún fi yé wa pé kí obìnrin lọ́mú kò lópin ẹwà..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ìmọ́tótó náà tún ṣe pàtàkì láti le è perí ọkùnrin wálé ìjìnlẹ̀ ohun ẹnu Ifá láti ọwọ́ Wade Abimbola apá kíní pg 51-25-26..
wikipedia
yo
SIYinka súnYinka Bmatiju bá ji à sinYinka Sókò pg..
wikipedia
yo
A kò gbọdọ̀ gbàgbé wípé ara ẹwà ìta tí Ọ̀rúnmìlà rí lára àwòrán ni ó fig bẹ̀ ẹ́ ní ìyàwó..
wikipedia
yo
Ṣugbọn ó jẹ́ ohun ìyàlẹ́nu pé bí àwòrán ti jọjú tó kọ ìwà àròkọ tí ìfà ń fi èyí pa ni pé ẹwà kìí ṣe ogbó nìkan..
wikipedia
yo
Ifá wo ẹwà inú àwọn obinrin ni oríṣìíriṣi ọ̀nà ààbò jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún Ọ̀rúnmìlà nígbà tó lálejò mẹ́ta ikú, àrùn àti èṣù..
wikipedia
yo
Ààbò ló kó nǹkan ìlò ọkọ rẹ̀ lọ tà ní ọjà Ejigbomekan ni owó pọ́ọ́kú o ra oúnjẹ wọn si tọ́jú àwọn àlejò wọn..
wikipedia
yo
Ìwà tí ààbò wù yìí mú kí àwọn àlejò méẹ̀tẹ́ta wọnyi fi Ifá sílẹ̀ láìpa..
wikipedia
yo
Wọ́n fún Ọ̀rúnmìlà ní ẹ̀bùn kí wọn ó tó fi ilé rẹ̀ sílẹ̀..
wikipedia
yo
Inú Ọ̀rúnmìlà dùn nítorí ìwà ààbò àti orí rẹ̀ tí ó kọ́ ràn-án..
wikipedia
yo
Ọ̀dà owó awo kọ̀rọ̀ ààbò obinrin rẹ̀ - ùntí 20 1–2 Ifá ó sì ni ọ̀ọ́kán à á yọ ná ní Ọ̀rúnmìlà bá pe ààbò obìnrin rẹ̀ pé kí ó kó àwọn nnkan ìní òun lọ sọ́jà lọ tà..
wikipedia
yo
ìjìnlẹ̀ ohun ẹnu ifá ìwé kínníIfá fẹ́ ìwà náà gẹ́gẹ́ bí aya olè àti ọ̀bùn ayé ni ìwà jẹ́..
wikipedia
yo
Èyí mi ki Ọ̀rúnmìlà le è lọ kí ló sí nnkan ó bá gún régé mọ́ àwọn ènìyàn sá lọ́dọ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
Àpọ́nlé kò sí fún Ọ̀rúnmìlà mọ́ bíi tí tẹ́lẹ̀ ṣebí kò kúkú sí àpọ́nlé fún ọba tí kò ní olórí..
wikipedia
yo
Ká mú ragbá ká fi ta rágba ká mú ragbà ká t a ra ìwà là ń wá o, ìwà alárá ò rí ìwà fún mi ìwà là ń wá ọ ìwà...Ìwà ni ó jé gégé bí orík aásì fún Orunmila ṣùgbọ́n kò mọ iyì ìwà ìwà afi afi tí ìwà fi ilé Orunmila sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí Ọ̀rúnmìlà fi gbé èmi ní ìyàwó kò bá lè ṣe rere láyé..
wikipedia
yo
Àwọn Yorùbá si gbàgbọ́ wipé ẹmi gigun ni san ìyà gigawù kò le gbàgbé emi nitori ohun rere ti èmi fun Ọ̀rúnmìlà ni ànfààní lati ṣe..
wikipedia
yo
Ìre gbogbo ti ẹ̀dá ń wá kiri ọwọ́ èmi ni gbogbo rẹ̀ wà..
wikipedia
yo
Àpà kínni òdù náà jẹ́ òkèn nínú àwọn ìyàwó Ọ̀rúnmìlà tí ò kọ orílé ràn án..
wikipedia
yo
Ó dìgbà tọ́mọ ẹ̀kọ́ṣẹ́ Ifá bá tó fojú ba òdù kó tó dẹni ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Èyí túmọ̀ sí pé babaláwo tí kò bá fọ́jú bọ̀bọ̀ ko tíì dáńgájíá..
wikipedia
yo
Ẹní bá fọ́jú bọ̀bọ̀ yóò sì dáwọ́ a fọ́jú bọ̀bọ̀ á rí obìnrin gẹ́gẹ́ bí olubiàbùdá kejì yìí ni yóò tú tìfun tẹ̀dó ìhà kejì tí ìfà kọ́ sí àwọn obìnrin..
wikipedia
yo
Ifá ri àwọn obinrin gẹ́gẹ́ bi ẹni ibi, aláṣejù, òjòwú àti àjẹ́..
wikipedia
yo
Ó fi ìhà yìí hàn torí pé a kìí dára ká má kù síbì kan.Ifá fi wọ́n wé aláìgbọràn ewúrẹ́ tí wọ́n máa ń ṣe àtojúbọ̀ àwọn ohun tí kò kàn wọ́n..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ yẹ̀mọ̀ọ́ fẹ́ mọ ìdí agbára óoláàálá ọkọ rẹ̀ pẹlu ẹ̀dọ̀ tí ó fi ń pa ẹran ohun tojú tilé-túlẹ̀ aláìgbọràn ń rí ní ojú rẹ̀ rí lọ́jọ́ yìí..
wikipedia
yo
Ọ̀rúnmìlà sọ fún àwọn ìyàwó yòókù láti máṣe yọjú wo kunkùnlé obìnrin rẹ̀ tuntun..
wikipedia
yo
Ìyáálé pé àwọn yòókù láti lọ yọjú wo ìyàwó tuntun yìí inú bí ìyàwó túntu, ó sì jáde..
wikipedia
yo
Ó sì fi wọ́n rẹ́ bayi ni àjàkálẹ̀ àrùn sì wọlé tọ̀ wọ́n..
wikipedia
yo
A kò lè fi gbogbo ara dá Ìyáálé àti àwọn ìyàwó yòókù lẹ́bi torí Orunmila ti yẹ ki ó fi iyàwó tuntun han àwọn tó bá ni ilé ṣùgbọ́n ó kọ̀ kò ṣe èyí nipa ojú ti Orunmila fi wo obinrin ti a lè sọ pé Orunmila lo fi ọwọ́ ara rẹ da ilé ara rẹ rù..
wikipedia
yo
Ẹní bá wá wàhálà dandan ni kí orí i.ifá tún fi àwọn obìnrin hàn gẹ́gẹ́ bí òjòwú, tí wọn kìí fẹ́ kí ọkọ wọn fẹ́ ìyàwó mìíràn lé wọn àfi àwọn nìkan..
wikipedia
yo
Ẹsẹ̀ amọ̀mọ ni èyí kò yẹ kí ìfà máa fẹ́ ìyàwó lórí ara wọn..
wikipedia
yo
Ohun ti Ifá n sọ nibi ni pé obinrin kò ṣe fi inú han ṣùgbọ́n ìbéèrè ti a bá bi Ifá ni pé se ọkùnrin ni ó ṣe fi inú hàn..
wikipedia
yo
Bí ó ti wà ní Líkì ni ó wà ní gbanjà obìnrin lékè obìnrin lọ́dálẹ̀ kénìyàn ṣe pẹ̀lẹ́ kí ó má finú han f'oo·ll Adéoyè pg 243 ẹ̀sẹ̀ ifá kan nínú Ọ̀bàrà méjì)ifá tẹ̀ síwájú nípa pípè àwọn obìnrin ní dokòdokò àti alágbèrè..
wikipedia
yo
Èrò ifá ni pé alẹ̀ yíyan yìí kìí jẹ́ kí wọ́n níí lọ́pọ̀ ìgbà pé ẹni tó bá kéré sóko ni wọ́n máa ń bá dáléásúnsùn, the un Ifá priest you have been seeing bad things, Worse things are yet to come; Worse things the father of bad things Ifá divination was performed for ágbìgbò who was going to the house of onkòròmẹ̀bi to perform divinationKirisẹ́ńdọ̀mù, husband of an ibùdótèròus wife it was because of the ínin adulwuni of his wife that oníwórónebi performed divination ìgbà tí ó fìyà jẹ obinrin náà tán ó gbé jù, àgbàlá ó sì dè é lókùn mọ́lẹ̀ ní àgbàlá ní oníkóró fi ìyàwó rẹ̀ sí tí ó fi lo bÍfá léèrè àgbìgbò ni kí oníkórówo ó ṣe sùúrù ó ní ẹni tí ó tóríi rẹ̀ bi Ifá léèrè ḿbẹ plot nínú àgbàlá ìgbà tí oníkóró gbọ́ ojú tí ì kò leè lọ tú ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ mọ́ ọ ní kí áas àas lọ bá òun tú u sílẹ̀ ìgbà tí a débẹ̀ dípò kí ó tú obìnrin náà sílẹ̀ ìwé ní ń fẹ́ ẹ.... (Ifa Poetry pg 87-42)Nígbà tí ìyàwó oníkóró náà yan babaláwo tí wọ́n ní kó bá wọn wò àìsàn àgbèrè àgbèrè lára rẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ọjọ́ yìí ni ibi wọn wọlẹ̀ nítorí bíbẹ́ ní oníkóróẹ̀bi bẹ àwọn méjèèjì..
wikipedia
yo
Babaláwo ti won ni ko wo aya oníkórówo ko ni eto lati se eyi..
wikipedia
yo
Fi obìnrin ẹ yalé yalé aláìnísuru a ri eleyi ninu sixteen great poems of Ifá not long again..
wikipedia
yo
They sent for Ọ̀rúnmìlà in the Àbọ̀dé of Olókun When Ọ̀rúnmìlà was going he did not take orò his wife along he promised to return on the seventeenth day..
wikipedia
yo
He also gave her clothes and plenty of food in the third month that òrumila had stayed away..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ met onígọ́ọ̀sùn after they had talked together onígọ́ọ̀ta gave her ten òkè measuresósó cowries and conigbati with her and again she became pregnant not long again orò met a man named Oluúkò he gave har ti ty oke measures of cowries after they amí fun with each other orò became pregnant again..
wikipedia
yo
All together the children of orò thus became six and they were all boys out of the six children three were children of concubines..
wikipedia
yo
Nínú ẹsẹ ifá yìí fi hàn wá wípé owó l'obìnrin mọ́ gbogbo àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta tó bá dalẹ̀ yìí ọwọ́ ni wọ́n fi han ọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Arítẹnimọ̀ọ́ wí, a fi àpãdì fẹ̀ǹfẹ̀ bò tirẹ̀ mọ́lẹ̀ ní ifá ìbéèrè tí a bá bi Ọ̀rúnmìlà nipé Ẹ ṣe kò bá obìnrin kankan ní àjọṣepọ̀ ní ìrìn àjò rẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n fọre sú Ọ̀rúnmìlà nílé ayé pé àwọn ò ní sọ̀kalẹ̀ ní ikùn rẹ̀ mọ́ àfìgbà tó bá rúbọ..
wikipedia
yo
Wọ́n ní kí ni ń jẹ́ sísọ kálẹ̀ wọn ni a tún sọ̀kalẹ̀ mọ́ Ọ̀rúnmìlà tí mo oko ní oko ikún tó gbin ẹ̀pà síbẹ̀..
wikipedia
yo
Ó mọ̀ pé ìhòhò ni àwọn ẹlẹyẹ wà kó tó gbà láti ṣe wọ́n ní àánú..
wikipedia
yo
Ọ̀rúnmìlà ti gbàgbé pé bí ọjọ́ oore bá pé aṣiwèrè a gbàgbé àti pé ìwọ̀n ni oore..
wikipedia
yo
aláwòmọ́ àti alákòóbá ni wọ́n gẹ́gẹ́ bí ìwà tí ìyá arúgbó tí a fi ṣe àpẹẹrẹ nínú Ọ̀yẹ̀kú méjì wú..
wikipedia
yo
Nígbà tó fọ̀rọ̀ iṣu lọ ẹnìkan tí kò gbà á jẹ ó fi owó epo sàmì síi lára..
wikipedia
yo
Ninu meji yemọ̀ọ́ iyawo oriṣa ńlá ló jí omi àwọn ẹlẹyẹ pọn tó so tún fọ aṣọ ọdẹ rẹ̀ sínú odò náà the witches asked, did she stab herself and ẹ̀lulu replied she did not stab herself, the blood was from her private part (the 16 great em Ifá) the witches therefore swallo both the husband and the wife..
wikipedia
yo
Aláṣejù baba àṣetẹ́ tún ní Ifá fẹ́ wọn ohun tí wọ́n ṣe náà nìyí tí ó jẹ́ kí nǹkan bọ́tí mọ́ wọn lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n dé ilé ayé osùn tí ó jẹ́ obinrin ààrin wọn ni ó máa ń ṣe ìpèsè fún àwọn ẹ̀mí àìrí yìí..
wikipedia
yo
Ní kàyéfìgọ̀ ìgbà tí wọ́n bat í ń lọ gbé ẹbọ yìí lọ fún àwọn ẹ̀mí àìrí yìí ọ̀ṣun kìí tẹ̀lé wọn, tí wọ́n bá ti dé ibẹ̀ gbogbo àwọn òrìṣà wọ̀nyí ló máa ń kó gbogbo isè yìí jẹ, ṣùgbọ́n wọ́n kò mọ̀ wípé Olódùmarè ti fún Ọ̀ṣun ní agbára láàrin wọn nígbà tó ya gbogbo nnnkenn kò gún régé mọ́ wọ́n sa ogun títí kò jẹ mọ́..
wikipedia
yo
Bayi ni wọn se pinu laarin ara wọn lati rán nla nla lọ sọ́dọ̀ Olódùmarè ṣùgbọ́n òrìṣà ńlá kọ̀ láti lọ..
wikipedia
yo
Ni ifa ba ni ki wọn ran ohun lọ sọdọ Olodumare nigba ti Ifa de ibẹ̀ lo ba sọ fun Olodumare wipe nǹkan ko gún régé mọ ọ..
wikipedia
yo
Olódùmarè bá ni osùn ń kọ́ ọ ní gbogbo nǹkan tẹ̀ ba tí ń ṣe é fi t'obinrin sí..
wikipedia
yo
Bayi ni gbogbo àwọn òrìṣà yòókù bù lọ sí ọ̀dọ̀ Osun láti bẹ́ẹ̀ ṣùgbọ́n osùn kò gba ebè bẹ́ẹ̀ lọ bẹ̀rẹ̀ sí ní mú gbogbo wọn bú lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan láti orí óosálà, Ọ̀rúnmìlà sùngó, Ọya Ọbalùfọ̀n àti bẹ̃bẹ lọ ó ní nǹkan tí wọ́n jọ rán àwọn ń kọ́? Ló bá sọ fún wọn wípé ọmọ tó wà ní ikùn ohun tí òhun bá fi bí obìnrin Olódùmarè yóò fi àwọn ẹlòmíràn dípò wọn..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n tó bá jẹ́ pé ọkùnrin ni ọ̀hún fi bí ó ni òhun yóò fi wọ́n sílẹ̀ wípé ohun náà ti ni lára wọn nìyẹn ni osùn bá fi oyin rẹ̀ bí ọkùnrin láti ìgbà yìí tí wọn bat í ń lọ sí igbó ẹ̀mí àìrí láti lọ run wọ́n máa ń lọ gbé ọmọ Ọ̀ṣun láti fi ọwọ́ tirẹ̀ náà sí gbogbo nǹkan tí wọ́n bá ń ṣe tán bá ṣe tán wọ́n á dá padà fún ìyá rẹ̀..
wikipedia
yo
Igbà yìí ló ti sọ pé tó bá jẹ́ ọkùnrin kó má jẹ́ Akin ọ̀ṣọ́..
wikipedia
yo
Ní kí a ka kúnlẹ̀ kí obìnrin obìnrin lọ bí wa ká tó di ènìyàn …ifá jẹ́ ká mọ̀ wípé alágbára ni àwọn obìnrin Olódùmarè ló pín wọn ilẹ̀ agbára yìí..
wikipedia
yo
Gbogbo bí àwọn òrìṣà yòókù ṣe ń kó ìpèsè yìí jẹ́ osùn mọ́ sí ṣùgbọ́n ó ṣe bí ẹnipé òhun kò mọ nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀..
wikipedia
yo
alágbára ni wọ́n bí wọ́n ṣe le lo agbára wọn láti fi ṣe dáradára ni wọ́n fi le ṣe búburú..
wikipedia
yo
(Olóyè Babalọlá Fatóògùn (Ifa priest) Ìbubu Òṣogbo.) tún sọ ìtàn nípa àwọn obìnrin àjọ àti ìpàdé tó máa ń ṣe ó fi hàn bó fẹ́ lo agbára akitiyan láti fíg bẹ ọ̀rọ̀ kalẹ́ ní gbogbo ìgbà tí wọ́n bá ti fẹ́ ṣe ìpàdé..
wikipedia
yo
Ni ọpọlọpọ igba gbogbo agbara káwọn to ba sọ labẹ gé..
wikipedia
yo
Nítorí ó dúró gẹ́gẹ́ bí agbára ìtúsílẹ̀ àti agbára Hayéṣe..
wikipedia
yo
Bó ṣe di ọjọ́ kan àwọn ọfà wá ọ̀nà láti jí agbára náà gbé wọn kò rí bí wọ́n ṣe lọ bá ìyàwó Ọ̀rúnmìlà píyí pé tó bá júwe ibi tí agbára ọ̀hún wà fún àwọn àwọn ó fún lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Ìyàwó Ọ̀rúnmìlà gba owó, ó sì gbé agbára náà ó lọ bọ́ mọ́ inú eérú ojú aró..
wikipedia
yo
Nígbà tí Ọ̀rúnmìlà fẹ́ ṣe ìpàdé a kọ́kọ́ gbìyànjú láti bi ìfà léèrè lórí bí ìpàdé yóò ṣe rí ni wọ́n ban ì kó lọ bó Ṣàngó ojú eérú torí kẹ̀ nǹkan bá le sẹ́nu ire àti pé kí àṣírí tó farasin lè bá hàn sáyé..
wikipedia
yo
Ìgbà tí Ọ̀rúnmìlà ti gbé eérú ojú ààrò láti bó Ṣàngó tán ló bá rí agbára rẹ̀ ti ọta tó ń pè ní ìyàwó bọ mọ́ inú eérú náà..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ọ̀tá ri pé wọn kò ri Ọ̀rúnmìlà mú náà bá tún lọ bá ìyàwó rẹ̀ láti tún ta ète mìíràn ìyàwó Ọ̀rúnmìlà pẹ̀lú àwọn ọ̀tá náà bá gbìmọ̀ láti lò ju agbára rẹ̀ sínú odó..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ọjọ́ àjọ ń pé bọ́ Ọ̀rúnmìlà lọ bi ìfà léèrè bí ọjọ́ àjọ yóò ṣe rí nítorí ó ti mọ bí obìnrin ṣe jẹ́..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ẹbọ tó jáde sì nip é kí ó lọ ní ẹja aborí ńlá kan, obì àbàtà, àti iyán ìlẹ̀kẹ̀ kò fi bo Ẹlẹ́dã rẹ..
wikipedia
yo
Líla ti Ọ̀rúnmìlà la inú ẹja lọ bá agbára rẹ̀ nínú ẹja..
wikipedia
yo
(Láti ẹnu dro Agbaje tí wọ́n gbà lẹ́nu babaláwo) itan kan ti Ifá sọ fí obìnrin han gẹ́gẹ́ bí Odele, áfénìmade olubi ènìyàn..
wikipedia
yo
Ifá sọ ìtàn nípa Ọ̀rúnmìlà ẹni tí mo fọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wò.Olóyè Babalola fàlógun Ifá priest ìlòbu Òṣogbo.Yorùbá..
wikipedia
yo
Ìṣiròyẹmíyẹmí, olùlóhùnlóhùnmí olùjọlá àwọn Yorùbá ní ọ̀nà tí wọ́n ń gbà ṣe ìṣirò, bẹ́ẹ̀ ni àti ọmọkékeré ni àwọn Yorùbá ti ń kọ́ ọmọ wọn ní ìṣirò ní ṣíṣe..
wikipedia
yo
Wọ́n yóò ní kí ó máa fi ẹni, èjì kọrin, ṣeré bíi ẹni bí ẹni ní ọmọdé ńkáwọ́ èjì bí èjì ní àgbàlá ń tàẹ́tá bí ẹtá ẹ jẹ́ ká tarawá lọ́rẹ ayọ̀ tí tà náà tún jẹ́ ọ̀nà tí àwọn Yorùbá fi máa ń kọ ìṣírò Yorùbá ní àwọn ọ̀nà tí wọ́n fi ń ṣe ìṣirò wọn fún àpẹẹrẹ "lé", "Dín", "Àádọ́Àádọ́ta", "Efin", – jẹ́ àwọn ọ̀nà fún ìfilé àti ìyọkúrò ìṣirò wọn..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ Ìṣirò Yorùbá–2- 10-Ẹwà 20–ogún 21–ọ̀kan lé lógún (20+1 = Ọ̀kan lé ní Ogún)26-dínlọ́gbọ̀n (30-4–4 = Ọgbọ̀n dín mẹrin)Ọgbọ̀n-ọgbọ̀n 40-ogójì (202 = ogún méjì) 60–ọgọ́ta (20x3 ogún mẹ́ta)100-ọgọrun-un (20x5) = ogún lọ́nà márùn-ún) 120–ọgọfa (20x6 = ogún lọ́nà mẹ́fà) 50–àádọ́ta (20 x3 = 10, ẹwàa dín nínú ogún mẹ́ta) 200–ìgbà 240-òjìlélúgba (40+200; òjì = 40) 300-ọ̀ọ́dúnrún 340-ọ̀tàdín nírínwó (400-60 = ọ̀tá = 60 Ìlànàta)800 àti igba mẹ́rin 200x)900-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún (1000-100 = Ọgọrun-un din ní ẹgbẹ̀rún1000-ẹgbẹrun 1600-ẹgbẹ̀jọ (200x8 = ìgbà mẹ́jọ 2000-Ẹgbẹon (Ẹgbàá) (200x10 - ìgbà ní ọ̀nà mẹ́wàá) 4000-ẹgbaaji (2000×2) 6000-ẹgbàáta (2000:x) Ẹẹdẹgbaarin (8-100 = Ọgọrun-un, din ninu ẹgbaarin (800) 10, 000 ẹgbàárùn-ún (Ẹgbẹ̀rún-ún àádọ́ta Ẹgbẹ̀rún-ún - Àádọ́ta Òkè-Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ní ìdàkejì ẹ̀wẹ̀, ìkọ́ni leè túmọ̀ sí ìbáwí tàbí ìtọ́sọ́nà láti ọ̀dọ̀ ẹnití ó ju ẹni lọ..
wikipedia
yo
Àmọ́ kí a máa fi ọ̀pá pooọló pa ejò, ìkọn tòní dá lórí ti òye, ìmọ̀ tàbí ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Ti bá ni kí a wòó bí ìtàn ìkọ́ni ṣe bẹ̀rẹ̀, a máa tọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Adáhùn sọ pàtó ibi tí ìkọ́ni ti bẹ̀rẹ̀, nítorí pé orílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan àti àkójọpọ̀ àwọn ènìyàn níbikíbi lóní ìlànà tí wọ́n ń gbà kọ́ àwọn ènìyàn tiwọn..
wikipedia
yo
Ṣugbọn orílẹ̀ èdè bíi Gíríìsì (Greece) tí ìṣirò ti bẹ̀rẹ̀, ilẹ̀ Lárúbáwá (Arabia), ilẹ̀ isGíríìkì ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, wà ninu àwọn irú eniyan tí ó tayọ ninu ètò ìkọ́ni..
wikipedia
yo
Àmọ́ ètò ìkọ́ni bí a ṣe mọ́ ti di àtọwọ́dọ́wọ́ débi wípé olúkúlùkù Lọ́tì gbáà tí wọ́n sì ti fi tún orílẹ̀ èdè wọn tó..
wikipedia
yo
Bí a ti ṣe ń kọ́ni ṣe ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ láwùjọ, bí àti ṣe leè kọ́ ọmọdé yàtọ̀ sí bí àti ṣe leè kọ́ ọ̀dọ̀ langba bẹ́ẹ̀ ni ti ọ̀dọ̀ langba náà yàtọ̀ sí ti àgbàlagbà..
wikipedia
yo
Gbogbo wa lamọ̀ wí pé ọmọdé a máa tètè kọ́ ẹ̀kọ́ láti ibi àwòrán, àwọ̀ àti àfihàn..
wikipedia
yo
Nítorí ìdí èyí, àwọn ìwé ti alakọbẹrẹ bíi Aláwìíyé dára púpọ̀ fún ẹ̀kọ́ àwọn ọmọdé..
wikipedia
yo
Ẹ̀wẹ̀, tí àwọn ọmọdé wọ̀nyí bá dèé ilé ẹ̀kọ́ girama ìlànà kíkọ́ àti mímọ́ wọn yóò ti yàtọ̀ díẹ̀ sí ti ilé ẹ̀kọ́ alakọbẹrẹ..
wikipedia
yo
Ní pẹ̀lẹ́ yìí, a óo ti máa fi yé wọn bá wọn ṣe lè fi ọwọ́ ara wọn see àwọn ohun tí wọn ń kọ́ wọn wọnyi, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni wọn óo ti máa gbáradì fún ilé ẹ̀kọ́ gíga..
wikipedia
yo
Ní ilé ẹ̀kọ́ girama ẹ̀wẹ̀, àwọn ohun tí àwọn akẹ́kọ óò máa há sórí - àkọ́sórí àwọn akẹ́kọ yóò dín kù, yàtọ̀ sí tíì Ilé Ẹ̀kọ́ ‘Oòsìtàbi
wikipedia
yo
Ǹjẹ́ tí àbá dé ilé ẹ̀kọ́ gíga, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìyàtọ̀ ni yóò ti wà nínú bí àṣẹ ń kọ́ni..
wikipedia
yo
Ile Eko giga ile ogbon, ile eko giga ile ominira..
wikipedia
yo
Ní ilé ẹ̀kọ́ gíga akẹ́kọ ní ànfààní láti ṣe ohun Towùú nígbà tí ó bá fẹ́ tí kòsí olùkọ́ tí yóó náà lọ́wọ́ wọ̀..
wikipedia
yo
Ìkọ́ni nílé ẹ̀kọ́ gíga yàtọ̀ gédégédé sí ti ilé ẹ̀kọ́ girama tàbí alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ilé ẹ̀kọ́ gíga, akẹ́kọ ló nílò láti ṣe iṣẹ́ jù, nítorí pẹ́ẹ́; ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, olùkọ́ yóò kàn wá láti tọ́ akẹ́kọ sọ́nà ní, akẹ́kọ ni yóò ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ fún ra rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìkọ́ni ní orílẹ̀-èdè yí ti dojú kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìsọ̀rọ̀ ti òṣì tí ń ṣe àkóbá fún ètò ọrọ̀ ajé àti ìdàgbà sókè ilẹ̀ yí..
wikipedia
yo
Ti aba ni ki awoo lati igba iwase fun apẹẹrẹ, eto ikọni dara ni ile ẹkọ alakọbẹrẹ, ede Yoruba ni afi hùn ko akeko lati ile ki Ato kii Ede omiran Bóo, amo ni bayii ede Gẹẹsi ni afi n ko akeko ti ọpọlọpọ wọn si n sọ ede Yoruba nile..
wikipedia
yo
Èyí lọ́mú kí ó jẹ́ wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ kò le sọ èdè Yorùbá kò já gaara láì ma fií èdè gẹ̀ẹ́sì kọ̀ọ̀kan bòó, bẹ́ẹ̀ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ kò sí lée sọ èdè Gẹ̀ẹ́sì dáradára..
wikipedia
yo