cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
YaKání gúsù apá ìwọ̀ oòrùn Congo ti Zaire ati ní Angola ni àwọn ènìyàn yàká wá..
wikipedia
yo
Lára àwọn aladugbo wọn ní suku, Teke àti nkanu.' Ìtàn Àtẹnudẹ́nu fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé àwọn ènìyàn yàkà pẹ̀lú ṣúkú jẹ́ ara àwọn tí ó kógun ja ìlú nlá kóńgò ní ẹgbẹ̀rún ọdún kẹrìndíngùn..
wikipedia
yo
Ṣùkú ti jẹ́ ọ̀kan lára kéréje ẹ̀yà tó wà lábẹ́ yaká rí. Nípa ṣíṣe òde ni ọ̀nà tí àwọn ọkùnrin yàká ń gbà ṣápẹ́ wọn láti gbé ètò ọrọ̀ ajé..
wikipedia
yo
Àgbẹ̀ ni àwọn obìnrin yáka, wọ́n sì ma ń gbìn ẹ̀gẹ́, àkópamọ́, ẹ̀wà àti erèé miran.Afrika..
wikipedia
yo
Zuluawọn eniyan Zulu ni ẹya to poju ni orile-ede guusu Afrika..
wikipedia
yo
A mọ̀ wọ́n mọ́ ìlẹ̀kẹ̀ alárànbara àti agbọ̀n pẹ̀lú àwọn nǹkan gbígbẹ..
wikipedia
yo
Wọ́n gbàgbọ́ pé àwọn jẹ́ ìran tó ṣe lára olóyè kan láti agbègbè Congo, ní nǹkan ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn ni wọ́n tẹ̀síwájú sí gúsù..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn Zulu gbàgbọ́ nínú òrìṣà tó ń jẹ́ Ọlá|àlàáfíà gẹ́gẹ́ bí Aṣẹ̀dá wọ́n Orisha yìí kò ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú ènìyàn bẹ́ẹ̀ ni kò ní ìfẹ́ sí ìgbé ayé kọọkan..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn Zulu pín sí méjì! Àwọn ìlàjì ní inú ìlú nígbà tí àwọn ìlàjì yókù sì wà ní ìgbèríko tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ àgbẹ̀..
wikipedia
yo
Èdè yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè ìjọba mọ́kànlá ilẹ̀ South Africa..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ Yorùbá ni agbègbè ìgbèrò àṣà ilẹ̀ àwọn ọmọ Yorùbá ni ìwọ̀òrùn Áfríkà..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ Yorùbá fẹ́ láti Nàìjíríà, Benin títídé Togo, agbègbè ilẹ̀ Yorùbá fẹ̀ tó 142,114 kmkm 106,0 km inú rẹ̀ (74.6%) bọ́sí Nàìjíríà, 18.9% bọ́sí orílẹ̀-èdè Benin, àti 6.5% yìókù bọ́sí orílẹ̀-èdè Togo..
wikipedia
yo
Ilé ìgbérò àṣà Yorùbá yìí ni iye àwọn ènìyàn bíi mílíọ̀nù 55.Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá gẹ́gẹ́ bí ìwádìí Átanda (1980), bí àwọn Yorùbá ṣe dé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àsìkò tí wọ́n tẹ̀dó síbẹ̀ kìí ṣe ìbéèrè tí ẹnikẹ́ni lè dáhùn ní pàtó nítorí pé àwọn baba ńlá wọ́n kò fi àkọsílẹ̀ iṣẹ́ àti ìtàn wọn sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àjogúnbá..
wikipedia
yo
Àwọn ìtàn àtẹnudẹ́nu tí a gbọ nípa ìṣẹ̀dá yàtọ̀ sí ara wọn díẹ̀díẹ̀..
wikipedia
yo
Ìtàn kan sọ fún wa pé àwọn Yorùbá ti wà láti ìgbà ìwáṣẹ̀ àti láti ìgbà ìṣẹ̀dá ayé..
wikipedia
yo
Ìtàn ọ̀run pé kí o wá ṣẹ̀dá ayé àti àwọn ènìyàn inú rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìtàn náà sọ fún wa pé Odùduwà sọ̀kalẹ̀ sí Ilé-Ifẹ̀ láti ọ̀run pẹ̀lú àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀..
wikipedia
yo
Nípasẹ̀ ìtàn yìí, a lè sọ pé Ilé-Ifẹ̀ ni àwọn Yorùbá ti ṣe, àti pàápàá gbogbo ènìyàn àgbáyé..
wikipedia
yo
Ìtàn mìíràn tí a tún gbọ́ sọ fún wa pé àwọn Yorùbá wá Ilé-Ifẹ̀ láti ilẹ̀ Mẹ́kà lábẹ́ àkóso Odùduwà nígbà tí ìjà kan bẹ́ sílẹ̀ ní ilẹ̀ Arébíà lẹ́yìn tí ẹ̀sìn Islam dé sáàrin àwọn ènìyàn agbègbè náà..
wikipedia
yo
Àwọn onímọ̀ kan nípa ìtàn ti yẹ ìtàn yìí wò fínnífínní, wọ́n sì gbà wí pé bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ṣe é ṣe kí àwọn Yorùbá ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ara Mẹ́kà àti agbègbè Arébíà mìíràn kí wọ́n tó ṣí kúrò, ibi tí wọ́n ti ṣẹ̀ wá gan-an ní Íjíbítì tàbí Núbíà..
wikipedia
yo
Àwọn onímọ̀ yìí náà gbà pé Odùduwà ní ó jẹ́ olórí fún àwọn ènìyàn yìí..
wikipedia
yo
Kókó pataki kan ti a ri dìmú ni pé Odùduwà ni oludari àwọn ènìyàn ti ó wá lati tẹ̀dó sí Ilé-Ifẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ìtàn méjèèjì ti a gbọ́ ṣe sọ..
wikipedia
yo
Tí a bá yẹ ìtàn méjèèjì wò, a ó rí i pé kò ṣe é ṣe kí Odùduwà méjèèjì jẹ́ ẹnìkan náà nítorí pé àsìkò tàbí ọdún tí ó wà láàrín ìṣẹ̀dá ayé àti àsìkò tí ẹ̀sìn Islam dé jìnnà púpọ̀ sí ara wọn..
wikipedia
yo
Nítorí ìdí èyí a lè gbà pé nínú ìtàn kejì ni Odùduwà ti kópa..
wikipedia
yo
Ìdí mìíràn tí a fi lè fara mọ́ ìtàn kejì ni pé lẹ́yìn àyẹ̀wò sí ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ Yorùbá fínnífínní, ó hàn gbangba pé Odùduwà bá àwọn ẹ̀dá Ọlọ́run kan ní Ilé-Ifẹ̀ nígbà tí ó dé ibẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ìtàn kan dárúkọ agbọ̀nmiregun tí Odùduwà bá ní ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Eyi fihan pe kii ṣe òfìfo ni ó bá Ile-Ife, bi ko ṣe pe àwọn kan wa nibe pelu Aoridindin marungun..
wikipedia
yo
Èyí sì tọ́ka sí i pé a ti ṣẹ̀dá àwọn ènìyàn kí ọ̀rọ̀ Odùduwà tó jẹ yọ, nítorí náà, kò lè jẹ́ Odùduwà yìí ní Olódùmarè rán wá láti ṣẹ̀dá ayé gẹ́gẹ́ bí a ti gbọ́ ọ nínú ìtàn ìṣẹ̀dá..
wikipedia
yo
Lọ́nà mìíràn ẹ̀wẹ̀, a rí ẹ̀rí nínú ìtàn pé Odùduwà níláti gbé ìjà kọ́ àwọn ọwọ́ ènìyàn kan tí ó bá ní Ilé-Ifẹ̀ láti gba ilẹ̀, àti pàápàá láti jẹ́ olórí níbẹ̀..
wikipedia
yo
Ìtàn Mọ́remí Ajasoro tí ó fi ẹ̀tàn àti ẹ̀mí ọmọ rẹ̀ Ọkùnrin kan ṣoṣo tí ó bí gba àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀ lọ́wọ́ ìmúnisìn àwọn ẹ̀yà Ùgbò lè jẹ́ ẹ̀rí tí ó fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé Odùduwà àti àwọn ènìyàn rẹ̀ jà ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogún kí wọ́n tó le gba àkóso ilẹ̀ náà lọ́wọ́ àwọn ọwọ́ ènìyàn kan tí wọ́n bá ní Ilé-Ifẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìtàn àbáláyé ti sọ..
wikipedia
yo
Ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àwọn ènìyàn Yorùbá wà káàkiri ìpínlẹ̀ bí i mẹsan-an..
wikipedia
yo
Àwọn ìpínlẹ̀ náà ni ẹ̀dọ̀, Èkó, Èkìtì, kogi, Kuwàrà, Ògùn, Ondó, Ọ̀ṣun àti Oyo.Lóde òní, Yorùbá wà káàkiri ilẹ̀ àwọn aláwọ̀ dúdú (Áfíríkà), Amẹ́ríkà àti káàkiri àwọn erékùṣù tí ó yí òkun Àtìláńtíìkì ká..
wikipedia
yo
A lè ríwọ́n ní Nàìjíríà, Gánà, orílẹ̀-olómìnira Bene, Togo, Saró àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà àti àwọn erékùṣù káàkiri, a lè rí wọn ní Jàmáíkà, Kuba, Damadadì àti tóbẹ̃gó pẹ̀lú Pobasí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Yàtò sí ètò ìjọba olóṣèlú Awarawa tí ó fi gómìnà jẹ olórí ní ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan, a tún ní àwọn ọba aládé káàkiri àwọn ìlú ńláńlá tí ó wà ní ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
Díẹ̀ lára wọn ni Ọba Ìbìní, Ọba Èkó, Ewì ti Adó-Èkìtì, Ọbaro ti Okene, Àlàkẹ́ ti Abẹ́òkúta, Deji ti Àkúrẹ́, Òbàdàn ti Ìbàdàn, Ata-Ọjà ti Òṣogbo, sóun ti Ògbómọ̀sọ́ àti Aláàfin ti Oyo..
wikipedia
yo
Eto ni o sọ wọn di olori ìlú kéréje nitori pé Yorùbá gbàgbọ́ pé ilú kìí kéré ki wọn ma nii àgbà tabi olóri..
wikipedia
yo
Aláàfin ni a kọ́kọ́ gbọ́ pé ó sọ àwọn olórí báyìí di olóyè tí a mọ̀ sí baálẹ̀..
wikipedia
yo
Lábẹ́ àwọn olórí ìlú wọnyi ni a tún ti rí àwọn olóyè oríṣìíríṣìí tí wọ́n ní iṣẹ́ tí wọn ń ṣe láàrin ìlú, ẹgbẹ́, tabi ijó (ẹ̀sìn)..
wikipedia
yo
Lára irú àwọn oyè bẹ́ẹ̀ ni a ti rí oyè ajẹwọ̀, oyè ogun, òye afipádanilá, oyè ẹgbẹ́, oyè ẹ̀sìn àti oyè ti agboolé bíi baálẹ̀, ìyáálé, Akéwejẹ, olórí ọmọ-oṣù, ìyá ewé amẹ́réya, Mọ́gàjí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Èdè Yorùbá ni báyìí, tí a bá wo èdè Yorùbá, àwọn onímọ̀ pín èdè náà sábẹ́ ẹ̀yà Kwa nínú ẹbí èdè Niger-Congo..
wikipedia
yo
Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ẹ̀yà Kwa yìí ló wọ́pọ̀ jùlọ ní sísọ, ní ìwọ̀ oòrùn aláwọ̀ dúdú fún ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọdún..
wikipedia
yo
Àwọn onímọ̀ èdè kan tilẹ̀ ti fi ìdí ọ̀rọ̀ múlẹ̀ pé láti orírun kan náà ni àwọn èdè bí Yorùbá, Kru, Banle, Twi, Ga, Ewe, Fon, Edo, Nupe, Igbo, Idoma, Efik àti Ijaw ti bẹ̀rẹ̀ sí yapa gẹ́gẹ́ èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó dúró láti bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ọ̀dún sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Àwọn Ìpínlẹ̀ tí a ti lè rí àwọn tó ń sọ èdè Yorùbá nílẹ̀ Nàìjíríà norílẹ̀ èdè Bìní..
wikipedia
yo
Togo àti apá kan ní Gúúsù ilẹ̀ Amẹ́ríkà bí i Cuba, Brasil, Haiti, àti Trinidad..
wikipedia
yo
Ní gbogbo orílẹ̀-èdè tí a dárúkọ, yàtọ̀ sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òwò ẹrú ni ó gbé àwọn ẹ̀yà Yorùbá dé ibẹ̀.Àṣà Yorùbá ìran Yorùbá jẹ́ ìran tó ti ni àṣà kí Òyìnbó tó mú àṣà tiwọn dé..
wikipedia
yo
Wọ́n ní ìgbàtbọ́ nínú Ọlọ́run àti òrìṣà, ètò ọ̀rọ̀ ajé wọ́n múnádóko..
wikipedia
yo
Yorùbá ni ìlànà ti wọ́n ń tẹ̀lé lati fi ọmọ fọ́kọ tàbí gbé ìyàwó..
wikipedia
yo
wọn ní ìlànà tó sọ bí a ṣe n sọmọ lórúkọ àti irú orúkọ tí a lè sọ ọmọ torí pé ilẹ̀ là á wò, kí a tó sọmọ lórúkọ..
wikipedia
yo
Ìlànà ati ètò wa tí wọn ń tẹ̀lé láti sin ara wọn tó papòdà..
wikipedia
yo
oríìṣíríṣìí ni ọ̀nà tí Yorùbá máa ń gbà láti ràn wọ́n lọ́wọ́, èyí sì ni à ń pe àṣà ìran-ara-ẹni-lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Àárọ̀, Igbe ọdún dìde, Ìsìngba tàbí oko Olówó, gbàmí-ó-rámì àti eéṣú tàbí eṣúṣú jẹ́ ọ̀nà ìran-ara-ẹni-lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Gbogbo ìgbésí ayé wọn ló wà létòlétò, èyí ló mú kí àwùjọ Yorùbá láyé ọjọ́un jẹ́ àwùjọ ìfọ̀kànbalẹ̀, àlàáfíà àti ìtẹ̀síwájú..
wikipedia
yo
Àwọn àṣà tó jẹ mọ́ ẹ̀tọ́ ìbágbépọ̀ láwùjọ Yorùbá ni ẹ̀kọ́-ilẹ̀, ètò-ìdílé, ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ tàbí ìròṣirò..
wikipedia
yo
Ẹ̀kọ́ Abini, àwòṣe, erémọdé, iṣiro, ìkíni, iwa Ọmọlúàbí, èèwọ̀, òwe Yorùbá, ìtàn àti àlọ́ jẹ́ Èkó-ilé..
wikipedia
yo
Ninu ètò mọ̀lẹ́bí láti rí baálé, ìyáálé ilé, ọkunrin ilé, obinrin ilé, ọbàkan, ìyekan, Erubílẹ̀ ati Arabatan..
wikipedia
yo
Oríṣìíríṣìí oúnjẹ tó ń fún ni lókun, èyí tó ń ṣeni lóore ati oúnjẹ amúnidàgbà ni ìran Odùduwà ní ní ìkáwọ́..
wikipedia
yo
Díẹ̀ lára wọn ni Iyán, Okà, ẹ̀kọ, Mọ́inmọ́in àti gúgúrú.Àwọn ìwé ìtọ́kasíAdéoyè, C.L..
wikipedia
yo
Ọ̀pádọ̀tun Tunji, ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá fún ilé-ẹ̀kọ́ olùkọ́ni agba, àkójọpọ̀ ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá.Yorùbá..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè YORÙBani orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àwọn ènìyàn Yorùbá wà káàkiri ìpínlẹ̀ bí i mẹ́sàn-án..
wikipedia
yo
Àwọn ìpínlẹ̀ náà ni ẹ̀dọ̀, Èkó, Èkìtì, kogi, Kuwàrà, Ògùn, Ondó, Ọ̀ṣun àti Oyo..
wikipedia
yo
Lóde òní, Yorùbá wà káàkiri ilẹ̀ àwọn aláwọ̀ dúdú (Áfíríkà), Amẹrika ati káàkiri àwọn erékùṣù tí ó yí òkun Àtìláńtíìkì ká..
wikipedia
yo
Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà àti àwọn erékùṣù káàkiri, a lè rí wọn ní Jàmáíkà, Kuba, Damadadì àti tóbẹ̃gó pẹ̀lú Pburaka àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Lára irú àwọn oyè bẹ́ẹ̀ ni a ti rí oyè ajẹwọ̀, oyè ogun, òye àfidanilá, oyè ẹgbẹ́, oyè ẹ̀sìn àti oyè ti agboolé bíi baálẹ̀, Ìyáálé, Akéwejẹ, olórí ọmọ-oṣù, Ìyá ewé amẹ́ré, Mọ́gàjí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ...
wikipedia
yo
A lè yígba yígba kí á wádìí lítítẹ́so fún àríyànjiyàn lórí mọ́fíìmù, ṣùgbọ́n lẹ́yìn gbogbo atótónu yìí, kí ni a rí? Ṣé ó lẹ́ni tó ń sọ Mọ́fíìmù tó dáwà tí wọn kìí sìí ṣe ọ̀rọ̀ fúnra wọn? Kí ni ó wà nínú ọ̀rọ̀-sísọ tó ní ìtumọ̀? Kí ni àwọn ìdánudúró fún gbólóhùn? Ọ̀rọ̀ ní àárín, inú, àti àwọn ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀.àjọmọ̀ ìbẹ̀rẹ̀, kódà fóníìmù pẹ̀lú kò lè dá dúró tí kò bá ti lè dìdí sí ìtumọ̀ nínú ọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Ó wà níbẹ̀ láti dá ayé òfo sílẹ̀, láti mọ̀ ati láti tún ọ̀rọ̀-sísọ mọ, láti fikùn, láti yọ kúrò ati láti mú yẹ̀ ní oríṣìíriṣi ọ̀nà.Ẹ jẹ́ kí á pada kúrò ní àníjẹ́ ìmọ̀ wa lọ sí Ajuwe ninu girama; ètò rẹ̀ ìlànà ìfojú- ààtò-wo ati àlàyé rẹ̀..
wikipedia
yo
Fífi ojú gbogbo ayé wo gírámà, a máa ṣe àpèjúwe ètò gírámà pẹ̀lú àwọn ọ̀rọ̀, ní ìbẹ̀rẹ̀, ní pàtàkì pẹ̀lú èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Yorùbá kí a sì fi àpéjọ àwọn ènìyàn tí ń gbọ́ ọ̀rọ̀ sílẹ̀ láti dásí ìfihàn nípa títẹríba fún èrò ìlànà tí a fi lélẹ̀ fún ìtúpalẹ̀ ní èdè tirẹ̀, èdè ènìyàn mìíràn..
wikipedia
yo
Àkíyèsí ni pé ti èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Yorùbá, àwọn èdè ti kò tan mọ́ra wọn tó gbilẹ̀, ni a lè tún ṣe àtúnṣe rẹ̀ sí àwọn òfin ti a ti gbìmọ̀ wọn níbí, ó ṣe é ṣe kí àwọn nǹkan tí a ń rò jẹ́ òtítọ́, kí ó sì ṣiṣẹ́ fún èdè mìíràn títí dé àwọn àbùdá àìròtẹ́lẹ̀ àwọn èdè kan..
wikipedia
yo
Nípa ti iye ìtẹ̀sí rẹ̀, a lè fi àwọn ọ̀rọ̀ mìíràn bí i kan tàbí náà kún ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ọ̀rọ̀ náà..
wikipedia
yo
Yíyẹ́ní láì ṣàlàyé tóbẹ̃ ẹ jùbẹ ẹ́ lọ girama rẹ̀ ní gbìmọ̀ tíọ́rì kan pé kí gbogbo àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ gba àwọn Atiku kan tàbí náà..
wikipedia
yo
Tí a bá ń fojú iṣẹ́ ọnà wò ó ọ̀rọ̀ kan tó jẹ́ x ní ìpín onítumọ̀ àdámọ̀ (ìsọ̀rí ọ̀rọ̀) Y ní Abgé tó ṣáájú ọ̀rọ̀mìíràn z, wíwà níbẹ̀ z jẹ́ wòfún..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ àfòyemọ̀ ti òkè yìí ni a ń pè ní pínbpín sí ìsọ̀rí tó múná dóko ni a jíròrò lé lórí nínú Yusuf (1997).Tí a bá padà sí àwọn àpẹẹrẹ (1,2) ti òkè, ẹni tí ń sọ̀rọ̀ lórí bí a ṣe lè mọ àwọn tí ó dá dúró yìí tó jẹ́ ọ̀rọ̀ orúkọ tí ó lè wà ní ipò tó ṣe kókó; Olúwa àti Abo..
wikipedia
yo
Lára àwọn ìmọ̀ rẹ̀ nípa àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ni pé a lè fún wọn ní àwọn ipá kan láti kó; tí a bá ní ká wò ó kí ní ìwúlò wọn tí wọn kò bá kó ipa kankan ní àyíká gbólóhùn tàbí òfo wọn..
wikipedia
yo
Fun apẹẹrẹ, ole kan jẹ oṣere, olukopa ti o ba kopa níhìnín tabi ohun lati mu Apiyada wa..
wikipedia
yo
Kódà kì í ṣe olè tí a kò bá mọ̀ ọ́ sí ẹni tó jí nǹkan kan nítorí nínú gbólóhùn bí i.5.Olè náà jí kálámùọ̀rọ̀ náà tó jẹ́ ‘Olè’ sọ ohun tó pọ̀..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀rọ̀ tó mú náà, tôjẹ́ Atiku, ó le yàtọ̀ fún òye àwọn olè àti pé ó jẹ́ òṣèré nínú ayé ọ̀fọ̀ tó le mú ìyípadà bá ìfarasin kálámù náà.Ranti pé ọ̀rọ̀ náà ‘kálàmù’ wà ní ìsọ̀rí yìí náà pẹ̀lú; ó máa gba Atiku náà/kan tí a lè gbékalẹ̀ ní ọ̀pọ̀ (àwọn kálámù) àti pé a fẹ́ fà á yọ, gẹ́gẹ́ bí àwọn ojúgbà rẹ̀, wí pé ó jẹ́ olùkópa ní àyíká gbólóhùn náà ṣùgbọ́n ní báyìí ó ń kó ipa ohun tí wọ́n jí, ipa náà ni a máa pè ní àkọ́so..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọ́ wá sọ fún wa pé kálámù kan lè jẹ́ ohun èlò fún ìbánisọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ipá náà, tí àwọn péjọBeti ńlá dúró fún ni à ń pè ní àwọn ipa aṣekoko, a le gé e kúrú sí ‘The - Roles', tí wọ́n máa ń kó gẹ́gẹ́ bí i ’o Role', Bí Ìtẹ̀síwájú bá ṣe ń bá ìtúpalẹ̀ wa..
wikipedia
yo
Kò lè sí ohun Ìtọ́kasí tó dúró, àwọn olùkópa kan tí a lè tọ́ka sí, nawọ́ sí, dárúkọ, sọ̀rọ̀ nípa, tí kò ní gbà 'Ó Role' kan..
wikipedia
yo
Àwọn àjọní tí a sábà náà ń rí ‘Ó Role' jẹ́ olùṣe, olùfaragbá, (nígbà mìíràn tí a máa ń pè ní àkọ́so), òpin àti èlò..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn onímọ̀ lìngúísíìkì mọ àwọn mìíràn dájú.Àwọn abúba àdámọ̀ ọ̀rọ̀ wa tí a le tọ́ka sí báyìí..
wikipedia
yo
Àwọn àbùdá mìíràn máa hàn kedere tí a bá gbé èdè tó yàtọ̀ sí èyí tí a ti mọ̀ tẹ́lẹ̀ yẹ̀wò..
wikipedia
yo
Ránti ohun ti a ro nipa girama Àgbáyé, Èdè Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Igbo, Èdè ‘Eskimo', Èdè ’69...
wikipedia
yo
jẹ́ díẹ̀ lára èdè ènìyàn tí wọ́n sí ní àwọn ìyàtọ̀ wọn, nínú ohun tó ṣe kókó báyìí, fífún àwọn ọ̀rọ̀ aṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ aṣẹ̀dá bí i òpó ‘Ó Role', àwọn ipò onítumọ̀ gírámà, abbl.Ẹ jẹ́ kí a fi àbùdá kan kún àwọn àpẹẹrẹ wa..
wikipedia
yo
Àwọn àkámọ́ tí a lò nínu apíntin sí ìsọ̀rí tó múná dóko àti àwọn tí a fihàn ní orí kìíní, ni a lè lò báyìí, bí i (t).7a.Ife kan (tó[tó kún] fún kọfí)btéèpù (mímọ́gaara) kan.Ọkùnrin (alágbára) kan.Àwọn ohun tí a fi sínú àkámọ́ ni à ń pè ní àwọn ìsọmọ, wọn kò ní apíntúnpín sí ìsọ̀rí, wọn kì í ṣe dandan, wọ́n jẹ́ ẹ̀pọ́n -ọ́n wòfún..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn wọ̀nyí tún wúlò níbo mìíràn, a fẹ́ yàn án pé kìí ṣe gbogbo àwọn ẹ̀pọ́n ló jẹ́ wòfún..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ, ọba tabi olórí kò níyì bí ọba tí wọn kò bá ní ìjọba tiwọn..
wikipedia
yo
Àkíyèsí pé láti sọ pé Ọba bìnrin náà, làá jẹ́ pé ènìyàn ń gbé nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì tàbí tí iye rẹ̀ sọ pẹ̀lú orílẹ̀ - èdè náà, máa ṣàì nítumọ̀..
wikipedia
yo
Orúkọ àbísọ lè tó láti mọ àwọn orí oyè, ṣùgbọ́n ìjọba wọn ti ṣe pàtàkì jù, ẹpọ̀n wòfún..
wikipedia
yo
Ní kukuru, àwọn ẹ̀pọ́n pp tí ọba àti ọba àti ọba jẹ́ wúnrẹ̀n tí a ní lọ.
wikipedia
yo
2.2Àkópọ̀ Ekuru kanàwọn ọrọ̀, ti a fihàn gẹ́gẹ́ bi i àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ, gba àwọn nǹkan mìíràn mọ́ra dandan, ‘Ibi’, àwọn ipa àṣekoko, isodo, àwọn kan- ńpa àti wòfún (àkámọ́), àwọn àfikún àti àwọn ìsọmọ bákan náà, àti àwọn mìíràn tí a kò mẹ́nu bà..
wikipedia
yo
Àwọn àbùdá àdámọ̀ tí olùṣọ́ èdè rẹ̀ gbọdọ̀ mọ̀ ni àwọn wọ̀nyí..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ dandan pé ó mọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀, lára èyí tí a máa sọ tó bá yá ní ìfìwàfìwà..
wikipedia
yo
A fẹ́ jẹ́ kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mọ̀ pé àwọn nǹkan wọ̀nyí jẹ́ àìkọ, lára àwọn akọwòó rìn ugh nínú A - Ọ̀rọ̀ náà (atúmọ̀ èdè ti iye náà)..
wikipedia
yo
A mẹ́nu bà á pé àwọn nǹkan wọnyi kìí handé bákan náà, ṣugbọn ó lè gbọ́n fara sin sinu àwọn kóòdù mọfọ́lọ́jì ninu ọ̀rọ̀ náà, ni àwọn àyíká tí a kọ fúnra sí.2.3 náà (2)àwọn àkójọpọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ tó yàtọ̀ sí ti àkọ́kọ́ máa fún wa ní àwọn nǹkan..
wikipedia
yo
That [s the NBA Examination is canCeled]]d.Put [X [נפשׁ Salt] [pp in the soap]]e.Saw [נפשׁ Moremi].Àwọn ọ̀rọ̀ ìṣe aláìgbabo ni a máa fihàn nísàlẹ̀, pẹ̀lú àwọn ìsọmọ.5kò sórí enib.Sunsun síjoko ẹ̀yin ọkọd.La aláe.kú.nígbà tí àwọn yìí kò gba àwọn àfikún, wọ́n le, nípa ìgbà àkànṣe gba àwọn abo - àwọn abo àkànṣe tí a so mọ́ wọn tàbí tí a ṣẹ̀dá láti ara wọn..
wikipedia
yo
Wọ́n fẹjọ́ èṣù sọ nínú Bíbélì pé ó ń gba Efa níyànjú láti má bẹ̀rù nípa jíjẹ èso èèwọ̀, tó wí pé, “Ẹ̀yin kò ní kú kan”
wikipedia
yo
Eṣú kò nílò àti yí ọ̀rọ̀ ìṣe aláìgbàbọ́ sí àgbàbọ̀nítorí pé wọ́n ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ wọn fi àwọn nǹkan pamọ́ lórí àwọn irú ọ̀rọ̀ orúkọ (kódà yíyípadà) ní àwọn èdè kan..
wikipedia
yo
Èdè Gẹ̀ẹ́sì kìí ṣe àpẹẹrẹ tó dára nípa bí ọ̀rọ̀ ìṣe ṣe le yí ọ̀rọ̀ Rouko tí a bá wẹ̀yìn, ipa aṣekókó òṣèré, àkọ́so, èlò, abbl wá tààrà tàbí àìṣetààrà láti ara ọ̀rọ̀ ìṣe..
wikipedia
yo
Fun bee olu ni osere ninu gbolohun mejeeji nigba ti ole naa je akoso ninu mejeeji bakan naa.A le soro nipa awon owo oro miiran, to yato si awon oro oruko ati awon oro ise, sugbon e je ki a pada seyin lati wo awon ijiroro wa fun ìbáramu..
wikipedia
yo
À ń sọ pé ọ̀rọ̀ kọ̀ọ̀kan, bó jẹ́ ọ̀rọ̀ orúkọ tàbí ọ̀rọ̀ ìṣe, máa ń wà pẹ̀lú àwọn nǹkan..
wikipedia
yo