cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní 1885, ìgbẹ́sẹ̀lé ìwọ̀oòrùn Afrika latọwọ àwọn ará Britain gba ìdámọ káríayé..
wikipedia
yo
Nígbà tó sì di ọdún tó tẹ̀le e, ilé-iṣẹ́ Royal Niger company jẹ́ Hiháyà lábẹ́ sir George Taubman Goldie..
wikipedia
yo
Ní 1900, àwọn ilé tí ilé-iṣẹ́ yìí ní di ti ìjọba Britain..
wikipedia
yo
ni January 1901, Nàìjíríà di sísọ-di-ọkàn gégé bíi ìlànà aláàbò..
wikipedia
yo
Nàìjíríà sì di ara ile-ẹyaọ̀ Britain tó wà lára alágbára nígbà náà..
wikipedia
yo
Ni 1914, agbègbè naa di sisọ-di-okan gege bii imusin ati aláàbò ilẹ̀ Nàìjíríà (Colony and Prounctorate of Nigeria)..
wikipedia
yo
Fun amojuto, Naijiria di pinpin si igberiko apa-ariwa, apa-guusu ati imusin Eko..
wikipedia
yo
Okòwò ayé òde òní tẹ̀ síwájú ní wàràǹṣeṣà ní Gúúsù ju ní àríwá lọ, ipa èyí hàn nínú ayé olóṣèlú Nàìjíríà òde òní..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejì gẹ́gẹ́ bíi èsì fún ìdàgbà ìsọníbiníbi Nàìjíríà àti Bíbéèrè fún Òmìnira, àwọn ìlànà-ìbágbépọ̀ tó rọ́pò ara wọn tí wọ́n jẹ́ ṣìsọ́dọ̀fin látọwọ́ ìjọba Britain mú Nàìjíríà súnmọ́ ìjọba-ara-ẹni tó dúró lórí aṣojú àti àpapọ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tó fi di àárín ọ̀rúndún 20jí, ìjàgbara fún òmìnira jà káàkiri Áfríkà.Lẹ́yìn òmìnira ní ọjọ́ kìíní, Oṣù Ọ̀wàrà, ọdún un 1960, Nàìjíríà gba òmìnira lọ́wọ́ orílẹ̀-èdè sísódòkan ìlú-ọba..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ Olómìnira Tuntun yìí mú kí ọ̀pọ̀ nínú àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè kí ẹ̀yà tiwọn ó jẹ́ èyí tó lágbára jù lọ..
wikipedia
yo
Ìṣèjọba àwa-ara-wá Nàìjíríà tuntun jẹ́ àjọṣepọ̀ àwọn ẹgbẹ́.Nigerian People's Congress ní ẹgbẹ́ ti àwọn ará àríwá tí wọ́n tún jẹ́ mùsùlùmí ń darí.Smi ti Ahmadu Aello àti Abubakar Tafawa Bewa tó di Alákóso èyí òmìnira..
wikipedia
yo
Ati ẹgbẹ eyitialákòóso agba ti awọn tiọmọ igbówọ́n jẹ ẹlẹṣin Kìrìstẹ́nì n jẹ idari National Council of Nigeria and the Cameroons , Nstac) ti Nnamdi aie, to di Gomina-Aayekoko ni ko ni 1960,ori Ooye I.Oni atakolegbeisiwaju Action Groupwa,ati awon Yoruba ti Obafemi àwse Woori olori..
wikipedia
yo
Ipinnu ọdun 1961 fun àpamo KameEléyìíta lati darapọ mọ orilẹ-ede Kameta nigbati Karí́ìsì Kame duro si Naijiria FA Buẹsẹ nitori pe apa Ariwa Wa tobi Jumo guusu lo gidigidi..
wikipedia
yo
Nàìjíríà pínyà lọ́dọ̀ Britani pátápátá ní 1963 nípa sísọ ara rẹ̀ di ilẹ̀ àpapọ̀ Olómìnira, pẹ̀lú Azikiwe gẹ́gẹ́ bí ààrẹ àkọ́kọ́..
wikipedia
yo
Rògbòdìyàn ṣẹlẹ̀ ní agbègbè apáìwọ̀òrùn lẹ́yìn ìbò 1965 nígbà tí í Nigerian National Democratic Party gba ìjọba ibẹ̀ lọ́wọ́ ó àgìjọba ológun àkọ́kọ́ àìdọ́gba yìí àti ìbàjẹ́ ètò ìdìbòyán tí olóṣèlú fà ní 1966 dé àwọn ìfipágbàjọba ológun léraléra..
wikipedia
yo
Àkọ́kọ́ ṣẹlẹ̀ ní Oṣù ṣeré tí àwọn ọ̀dọ́ olóṣèlú alápásì láá e Major Emmanuel Oajã àti Chukwuma Kaduna Nedtyl..
wikipedia
yo
Ó kù díẹ̀ kó yọrí sí rere – Àwọn Olùfipagba pa Alákòóso Àgbà, Sir Abubakar Tafawa Balewa, Aṣọlórí Agbegbe Aapawáfo Nàìjíríà, Sir Ahmadu Bello, ati Aṣọlórí Agbegbe Apáìwọ̀ìwọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà, Sir Ladoke Akintola..
wikipedia
yo
Bó tilẹ̀ jẹ́ báyìí, síbẹ̀síbẹ̀, àwọn olùfipágbàjọba náà kò lè bẹ̀rẹ̀ síní ṣe ìjọba nítorí ìṣòro bí wọn yíò ti ṣe, nítorí èyí nwáfor orízu, Adélédè Ààrẹ jẹ́ mímú dandan láti gbé ìjọba fún ilé-iṣẹ́ ológun adigun Nàìjíríà lábẹ́ é apàṣẹ ọ̀gágun jty Aguyí-Ironsi.Ìjọba àti ìṣèlúòfin irúfẹ́ òfin mẹrin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ló wà ní Nàìjíríà.
wikipedia
yo
Òfin ilée Gẹ̀ẹ́sì; tó wá láti ìgbà ìmúnisìn lọ́wọ́ bìrítani.
wikipedia
yo
Òfin tó wọ́pọ̀; tó jẹ́ ìṣẹ́jú àti didàgbàsókè lẹ́yìn ìmúnisìn.
wikipedia
yo
Òfin ìbílẹ̀; tó wá láti inú àwọn àṣà àti ìṣe káàkiri ilẹ̀ Nàìjíríà.
wikipedia
yo
Òfin sèríà; tó wá láti inú òfin ẹ̀sìn Islam, tí wọ́n sì ń lò láwọn ìpínlẹ̀ tó wà lápá àríwá Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Nàìjíríà ní ẹ̀ka ìdájọ́ ó ti ilé-ẹjọ́ gíga jùlọ ilẹ̀ Nàìjíríà, ó jẹ́ èyí tó lágbára jù lọ.ìbáṣepọ̀ òkèrè ní kété tí ó gba òmìnira ní 1960, Nàìjíríà sọ ìṣọ̀kan Áfríkà di Àárín-gbùngbùn òfin òkèèrè rẹ̀, ó sì kópa nlá nínu u ìgbógun ti ìjọba ìyàsọ́tọ̀-ẹlẹ́yàmẹ́yà ní South Africa..
wikipedia
yo
Ìyapa kan kúrò ní ìbáṣepọ̀ pẹ́kípẹ́kí ti Nàìjíríà bá Israel ṣe yípo gbogbo Lefi..
wikipedia
yo
Israel ṣonígbọ̀wọ́ àti àmójútó fún kíkọ́ àwọn ilé aṣòfin Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Àmọ̀ okeere Naijiria ri idanwo ni 1970s lẹ́yìn ti orílẹ̀-èdè náà jáde kúrò nínú ogun abẹ́lé NÍṢỌ̀KAN..
wikipedia
yo
Ó dúró tí àwọn akitiyan tó lòdì sí ìjọba àwọn ìjíran ìdùnwà ní ẹkùn gúùsù Áfríkà..
wikipedia
yo
Nàìjíríà dúró ti ẹgbẹ́ ẹ African National Congress pẹ̀lú u bó ṣe pọkàn pọ̀ nínú ìpinnu rẹ̀ nípa ìjọba South Africa àti àwọn ipa ológun wọn ní Gúúsù Áfríkà..
wikipedia
yo
Nàìjíríà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọ̀dàgbólóhùn ẹgbẹ́ ẹ̀ Organisation for African unity (tó di African Union) ó sì ti ní ipa tó kámọnmo ní ìwọ̀ìwọ̀ Áfríkà àti ní Áfríkà lápapọ̀..
wikipedia
yo
Nàìjíríà ṣe akitiyan ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ní ìwọ̀ìwọ̀ Afrika, ó sì tún ṣe aṣáájú fún Economic Community of West African States (Ríyìn) àti ÉECỌmọ (pàápàá nígbà ogun abẹ́lé ní Liberia àti Sierra Leone) – tí wọ́n jẹ́ ẹgbẹ́ ọrọ-ajé àti ti ológun ní ṣíṣẹ̀ntẹ̀lẹ́.Pẹ̀lú ìdúró tó so mọ́ Áfríkà yí, Nàìjíríà rán àwọn ikọ̀ lọ sí Congo ní ìtẹ́lẹ̀ ase àjọ àwọn orílẹ̀-èdè kété lẹ́yìn òmìnira (ó sì ti jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ láti ìgbà náà)..
wikipedia
yo
Nàìjíríà tún ṣe ìtìlẹ́yìn fún oríṣìíríṣìí ẹgbẹ́ ẹ Áfríkà àti àwọn Ìdìde fún ìjọba tiwa-n-tiwa ní àwọn 1970s, tó fi mọ́ kíkó ìtìlẹ́yìn jọ fún MPla ní Angola àti SWAPO ní Nàmíbíà, àti ṣíṣe ìtìlẹ́yìn fún àtakò sí àwọn ìjọba eléèyàn péréte tí àwọn Potogí ní Mozambique àti Rhodesia..
wikipedia
yo
Ní ìparí oṣù Belu ní 2006, Nàìjíríà ṣe Àkójọ Ìpàdé Ẹ̀ Áfríkà àti Gúúsù Amẹ́ríkà ní Abuja láti fi gbé nǹkan tí àwọn olùkópa kan pè ní ìbáṣepọ̀ “gúúsù-gúúsù” lóríṣiríṣii ọ̀nà lárugẹ..
wikipedia
yo
Nàìjíríà tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ilé-ẹjọ́ ìwàọ̀daràn káríayé àti àjọní àwọn orílẹ̀-èdè ..
wikipedia
yo
Wọn yóò kúrò nínú u taṣọgbẹ́yín fún ìgbà díẹ̀ ní 1995 nígbà ìṣèjọba Abacha..
wikipedia
yo
Nàìjíríà ti jẹ́ olùkópa takuntakun nínú Ọjà epo Àgbáyé láti 1970s,ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ẹ̀ OPEC, èyí tó darapọ̀ mọ́ ní 1971..
wikipedia
yo
Ipò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ọnta epo gbòógì jẹyọ nínú àwọn ìbáṣepọ̀ gbimi pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè tó ti dàgbà sókè, pàápàá Àmẹ́ríkà, àti pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè tó sì ń dàgbà sókè..
wikipedia
yo
Láti 2000, ìṣòwò láàrin ìkọ̀wé-Nàìjíríà ti ga sókè sí i..
wikipedia
yo
Ipòsíi nínú u owó tí lé ní mílíọ̀nù 10,384 dọ́là láàrín orílẹ̀-èdè méjèèjì láàrin 2000 sí 2016..
wikipedia
yo
Àmọ́, owó láàrín Ṣáínà àti Nàìjíríà ti di ọ̀rọ̀ òṣèlú nlá fún Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Èyí jẹyọ nínú u pé ìtajáde àwọn Ṣáínà jẹ́ ọgọ́rin nínú u ọgọ́rùn-ún gbogbo owó..
wikipedia
yo
Èyí mú àìdọ́gba wá, pẹ̀lú u bi Nàìjíríà ṣe ń kó ọjà ìlọ́po mẹ́wàá wọlé ju ti Ṣáínà lọ..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀, ọrọ-ajé Nàìjíríà ti ń faratì àwọn ìkọ́wọlé ọjà Olówó-pọ́ọ́kú láti fi gbéra, èyí si mú ìdínkù wá nínú u ìṣòwò Nàìjíríà lábẹ́ irú ètò bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ìtẹ̀síwájú pẹ̀lú u òfin òkèèrè tó so mọ́ Áfríkà, Nàìjíríà mú àbá wá fún níná òwò kan náà ní ìwọ̀ìwọ̀ Áfríkà tí a máa jẹ́ Ríyín lábẹ́ ẹ̀ èrò pé náírà ló máa wò ó dàgbà ṣùgbọ́n ní ọjọ́ kọkànlélógún, oṣù Ọ̀pẹ, 2019; Ààrẹ Alassane oúat ti Ivory Coast pẹ̀lú u Emmanuel Macron àti púpọ̀ nínú àwọn orílẹ̀-èdè Uebìne, kéde pé àwọn kan máa yí orúkọ Cfa Franc padà ní kàkà kí àwọn rọ́pò rẹ̀ bí wọ́n ṣe rò tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Ní 2020, wọ́n ti gbé ètò owó Ó túnja náà ti di 2025.Iṣẹ́ Ológunese àwọn Ologun Olómìnira ÀPApọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà ni láti dáàbò bo ilẹ̀ Nàìjíríà, gbígbésókè làgún abo Nàìjíríà àti ìtìlẹ́yìn ìkáka ìrírí àlàáfíà ní níìwọ̀ Áfríkà..
wikipedia
yo
iṣẹ́ ológun Nàìjíríà ní ilé-iṣẹ́ ológun Akọgun,Ilé-iṣẹ́ ológun ojú omi, àti ilé-iṣẹ́ ológun ojú afẹ́fẹ́.lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà,ilé-iṣẹ́ ológun Nàìjíríà ti kópa nínú ìgbèrò Àlàáfíà ní Áfríkà..
wikipedia
yo
Ile-ise ologun Naijiria gege bi i ikan ninu EComog ti kopa gege bi i olufbero Alaafia ni Liberia ni 1990, Sierra Leone ni 1995, Ivory Coast ati Sudan.Jirékọjá] Naijiria wa ni apa ìwọ̀oòrùn Afrika ni ìkún-omi Guinea, apapọ ile e re si fe nìwọ̀n 923,gen km (356,66 sq mi), eyi je ko je orile-ede 32ji to tobi ju lo ↑ awon Tanzania in Tanzania..
wikipedia
yo
Ibodè rẹ̀ pẹ̀lú Benin tó fọ́yín km, ti Niger to 1497 km, ti Chad to 87km àti ti Kamẹrúùnù to 16km km; bákan náà àlà etí-ọ̀dọ̀ rẹ̀ tó 853 km..
wikipedia
yo
Ibi to ga ju lọ ni Nàìjíríà ni Fibpál Waddi ni 24 M (7936 ft)..
wikipedia
yo
Àwọn ọdọ gbangba ibẹ̀ ni odò ọya ati odò Benue ti wọn ja pọ̀ ni lokọja, lati ibi ti wọn ti san lọ sinu Okun Atlantiki lati Delta Naija.Bakan naa, Naijiria jẹ gbọngan pataki fun oríṣìíríṣìí ẹranko ati nǹkan abẹ̀mí pàtàkì..
wikipedia
yo
Agbegbe to ni awọn oríṣìíríṣìí labalábá julọ laye ni agbegbe Calabar ni Ipinle Cross River..
wikipedia
yo
Awon Ọ̀bọ Àgbélé n gbe ni guusu-ila-oorun Naijiria ati Kamẹrúùnù nikan.Ojú Nàìjíríà je oríṣìíríṣìí..
wikipedia
yo
Ní gúúsù, ojú-ọjọ́ jẹ́ ti ọjọ́inúigbó àmúooru níbi tí ọjọ́ ọdọọdún tó 60-80 inches (1,524 — 2,032 mm) lọ́dún..
wikipedia
yo
Ní apá gúúsù-ìlà-oòrùn ni àwọn ìwúlé òbudu wà.Àwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà jẹ́ pípín sí mẹ́rìndínlógójì ìpínlẹ̀ 36 pọ́mọ agbègbè oluilu àpapọ̀ kan; àwọn wọ̀nyí náà jẹ́ pípín sí agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ 774..
wikipedia
yo
Nàìjíríà ni 2007 jẹ́ 37th lágbàáyé ní gbogbo ìpawọ̀ orílẹ̀-èdè..
wikipedia
yo
GẸ́GẸ́ BÍ Economic Intelligence unit àti ilé-ìfowópamọ́ àgbáyé ṣe sọ..
wikipedia
yo
Gbogbo ipawó orílẹ̀-èdè ti Nàìjíríà fún ìpín agbára ìrajà ti jẹ́ ìlọ́po méjì láti $170.7 lẹ́gbẹgbẹ̀rúnkejì ni 2005 de $292.6 lẹ́gbẹgbẹ̀rúnkejì ní 2007..
wikipedia
yo
Gbogbo ipawọ orílẹ̀-èdè fún ẹni kọ̀ọ̀kan ti fọ́ láti $69 fún ẹnì kọ̀ọ̀kan ní 2006 dé $1,754, fún ẹnì kọ̀ọ̀kan ní 2007..
wikipedia
yo
Nígbà ọ̀pọ̀ epo àwọn ọdún 1970s, Nàìjíríà dá gbèsè òkèèrè tó tóbi gidi láti sé ìnáwó ìde-ajé-mọ́lẹ̀, ṣùgbọ́n leyin ti iye owó epo din ní àwọn ọdún 1980s, ó ṣòro fún Nàìjíríà láti san àwon gbèsè rè padà, èyí fà kó fi owó tó yá sílè láìsan kò le bá a kọjú sí bí yíò ṣe san èlé ori owó tó ya nìkan.Lẹ́yìn ìjíròrò ìjọba Nàìjíríà ní October 2005, Nàìjíríà àti àwọn ásìni Paris Club fi ẹnu kò pé Nàìjíríà le ra gbèsè rè padà pèlú ìdinwó tó tó 60%
wikipedia
yo
Nàìjíríà lo eré tó jẹ níbi epo láti san gbèsè 40% tó kù, èyí jẹ́ kí $1.15 lẹ́gbẹ́ẹgbẹ̀rún kejì ó lè silẹ̀ lọ́dún láti ṣe ètò ìdin àìní..
wikipedia
yo
Nàìjíríà di orílẹ̀-èdè àkọ́kọ́ ní Áfríkà láti san gbogbo gbèsè (ti ìdíye rẹ̀ jẹ́ $30 lẹ́gbẹẹgbẹ̀rún kejì) tó jẹ́ Paris Club padà ní April 2006.apá okoòwò Nàìjíríà jẹ́ orílẹ̀-èdè gbẹkun tó ń ta epo Giko láyé, bẹ́ẹ̀ sì ni òun ní ikéẸwà tó ní ìpamọ́ epo Gete..
wikipedia
yo
Epo Petrole ko ipa pataki ninu u okoowo Naijiria to ṣirò fun 40% gbogbo ipa-wo orile-ede (Jèhófà) ati 80% iye owó ti ijoba n pa..
wikipedia
yo
Nàìjíríà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọjà fún ìbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kán tó ń dàgbà sókè kíakía jù láyé, àwọn ilé-iṣẹ́ ìbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kán bí i MTN, Etisálà, Airtel àti Globacom ni ibùjókòó tó tóbi jù lọ tó sì lérè jù lọ ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Nàìjíríà ní apá okoòwò iṣẹ́fúnni oní-Ìnáwó dídàgbà gidi, pẹ̀lú àdàlú àwọn ilé-ìfowópamọ́ abẹ́lẹ̀ àti káríayé, àwọn ilé-iṣẹ́ ìmójútó ohun ìní, ilé-iṣẹ́ adìyẹ, àwọn ilé-iṣẹ́ Brorakẹ̀rà, àwọn àjọ aládàáni Enisfail àti àwọn ilé-ìfowópamọ́ ìnáwólé..
wikipedia
yo
Bákan náà, Nàìjíríà tún ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan àlùmọ́ọ́nì àti ìmúlò bíi ẹ̀fúùfù aládàánidá, èédú, alàgbà, Ralíté, wúrà, tín, ìrìn inú-ilẹ̀, òkúta dídán, níobìni, òjé, àti Oríe..
wikipedia
yo
Bo tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn nǹkan àlùmọ́ọ́nì inú ilẹ̀ wọ̀nyí pọ̀ dáadáa, àwọn ilé-iṣẹ́ akó-àlùmọ́ọ́nì tí ó mú wọn jáde ó sí.Iṣẹ́ àgbẹ̀ jẹ́ èyí tó ń mú owó òkèèrè wọlé fún Nàìjíríà tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ ..
wikipedia
yo
Nígbà kan, Nàìjíríà ló ń ta ẹ̀pà, kòkó àti epo ọ̀pẹ tó pọ̀ jùlọ sí Òkè-Òkun àti olùpèsè pàtàkì Coconut, èso ọsàn, àgbàdo, ọká bàbà, ẹ̀gẹ́, iṣu àti ìrèké..
wikipedia
yo
Bí i 60% àwọn ará a Nàìjíríà ni wọ́n ń ṣiṣẹ́ àgbẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni ilẹ̀ tó ṣe é dáko sí wa ṣùgbọ́n tí wọn kò fi bẹ́ẹ̀ pọ̀ gidi ..
wikipedia
yo
Nàìjíríà ni àwọn ilé-iṣẹ́ àgbéṣe bí i Bẹ́n àti ìhun aṣọ ní Kano, Abeokuta, Onitsha àti ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Ile-ise Ato-oko-po bi i Peugeot lati Fránsì ati Bedford lati Britani to je apa kan lara ile-ise oko lati orile-ede Amerika, General Momasrs;gers-in, awon ẹwu t-rt, ike ati ounje alágolo.0b013erismpọ̀ iye awon eeyan Naijiria ni orile-ede ti eeyan posi julo ni Afrika bo tile je pe iye to je gangan ko i je mimo..
wikipedia
yo
Àjọ Ìṣọ̀kan Àwọn Orílẹ̀-Èdè Díye Pé Iye Àwọn Èèyàn tó wà ní Nàìjíríà ní 2009 jẹ́ 154,7,000,000, ti 51.7% nínú u wọ́n ń gbé ní ìgbèríko tí 48.3% sì ń gbé ní ìlú-ńlá ;àti iye ènìyàn 167.5 ní agbègbè ìlọ́po méjì kìlómítà kan..
wikipedia
yo
Nàìjíríà ní orílẹ̀-èdè kẹjọ tí ó ní àwọn ènìyàn tó pọ̀ jùlọ láyé..
wikipedia
yo
Onka ni 2006 fi han pe iye eniyan ti ojo-ori won wa laarin odun 0-14 je 42.3; laarin odun 15–65 si je 54.6%
wikipedia
yo
Òṣùwọ̀n ìbímọ pọ̀ gidi ju òṣùwọ̀n ikú lọ, wọ́n jẹ́ 40.4% àti 16.9% nínú ènìyàn ẹgbẹ̀rún (1000) ní tẹ̀léńtẹ̀lé..
wikipedia
yo
Nàìjíríà ní bí i ẹ̀yà 250 pẹ̀lú oríṣìíríṣìí èdè pẹ̀lú àṣà àti íṣe oríṣìíríṣìí..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn tó tóbi jùlọ ní Hausa/Fúlàní, Yorùbá àti igbó tí àpapọ̀ wọn jẹ́ 68% nígbàtí ẹ̀dọ̀, Ijaw, Kanuri, Ibibio, Èbìrà, Nupe àti Tiv jẹ́ 27%,tí àwọn yòókù jẹ́ 7%.Ó jẹ́ mímọ̀ pé àárín ìbàdí Nàìjíríà ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀yà bí i PIbùdóyẹn, GoeMai, àti Kofyar.Àwọn ìtọ́kasí àwọn orílẹ̀-èdè AFRIIAWọ́n orílẹ̀-èdè ìjọba àpapọ̀..
wikipedia
yo
Dori je eya kan lara awon olugbe meta awon eniyan orile ede Rwanda and Burundi ni apa arin Afrika..
wikipedia
yo
Ìyàtọ̀ díẹ̀ ló wà láàrin àṣà àwọn ará Tutsi àti Hutu..
wikipedia
yo
Àgbẹ̀ àti olùsìn màálù ní iṣẹ́ àárọ̀ àbínibí àwọn ará Tutsi..
wikipedia
yo
màálù jẹ́ ohun tí àwọn ará Tutsi fi máa ń fi agbára àti ọlá wọn hàn, èyí ló sì mú àwọn ará Tutsi jẹ olùborí nínú iṣẹ́ àgbẹ̀..
wikipedia
yo
Fún bí ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ọdún sẹ́yìn ni Tutsi tí ń ṣe ìjọba lórí àwọn tókù.Afrika..
wikipedia
yo
Trù tabi Batwa jẹ́ àwọn ẹ̀yà eniyan kúkúrú (pig) tí a lé pẹ̀ ní aràrá..
wikipedia
yo
Àwọn ni olùgbé tí a ní àkọsílẹ̀ pé ó pẹ́ jù ní àárín gbùngbùn ilẹ̀ Áfíríkà níbi tí a ti rí àwọn orílẹ̀-èdè bí Rwanda, burúnìdí àti ilẹ̀ Olómìnira ti Congo lóde òní..
wikipedia
yo
Àwọn ará Hutu tó ṣe wá láti àwọn ará Bantu jọba lè kúnwa lórí nígbà tí wọ́n dé agbègbè náà ṣùgbọ́n nígbà tó di bí ẹgbẹ̀rún ọdún iketiẹ̀ (15th century AD) ní Tust fò jẹ́ ara ẹ̀yà Bantu dé sí agbègbè náà tí wọ́n sì jẹ ọba lórí kúnwa àti Hutu tí wọ́n bá lórí ilẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Àwọn òyàn òru ń sọ èdè KW– èyí tí àwọn ènìyàn yọpọ̀ àti ṣeó ń sọ.Afrika..
wikipedia
yo
Èdè Wolof jẹ́ Èdè tí a ń sọ ní àti bèbè Senegal mílíọ́nù méjì-àbọ̀ niye àwọn tó ń sọ..
wikipedia
yo
Àwọn iṣẹ́ ọnà wọn máa ń rẹwà tó sì ma ń ni Àmín àti àwòrán àwọn aṣáájú nínú ẹ̀sin Mùsùlùmí..
wikipedia
yo
Ìtàn Wolof ti wà láti bí ẹgbẹ̀rún ọdún méjìlá tàbí mẹ́tàlá sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Ìtàn ẹbí alámọyìdẹ́nu wọn sọ pé ọ̀kan lára àwọn tó kọ́kọ́ tẹ̀dó síbí yìí jẹ́ àwọn tó wá láti orífún Fulbe..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtàn Wolof ni a le rí nínú àwọn orin oríkì èyí tí a ma ń gbọ́ láti ẹnu àwọn 'bl'ots' àwọn akéwì..
wikipedia
yo
Woyónì Agbegbe Congo (Zaire) ni a tin i awon eyan wọ̀yọ̀..
wikipedia
yo
Ní nǹkan ẹgbẹ̀rún ọdún kẹẹ̀dógún (prior 15th century) ìtàn ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ pé Ọmọọba bìnrin ńwẹ̀ kó àwọn ènìyàn rẹ̀ tó yé kan di wọ̀yọ̀ sọdi lọ sí ojú gbangba níbi tí wọ́n gbé wá báyìí..
wikipedia
yo
A pa ìlú wọn àkọ́kọ́ run nígbà tí Ọba kíkọ́NGO tó jẹ́ olùbágbé wọ́n kógun jàwọ́n..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ àgbẹ̀dẹ àdému apẹja àti ọdẹ jẹ́ àwọn iṣẹ́ ọkùnrin wọ̀yọ̀..
wikipedia
yo
Wakoko je ilu ni Kamerunonapa ariwa Cameroon ni ibugbe awon eniyan wum..
wikipedia
yo
Nítorí igbagbọ wọn nípa orí, kò fèsì ninu iṣẹ́ ọnà wọn tí a kì í rí àwòrán orí..
wikipedia
yo
Agbe Ologin Àgbàdo, iṣu, àti ewébẹ̀ ni àwọn ara wúm..
wikipedia
yo
Wọ́n tún jẹ́ olùsìn adìẹ àti ewúrẹ́ èyí sì kó ipa tó jọjú nínú àtijẹ wọn lójojúmọ́..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Fúlàní ló di Mùsùlùmí ní òpin ẹgbẹ̀rú ọdún méjìdínlógún..
wikipedia
yo
Akitiyan wọn ninu ẹ̀sìn yìí lati tan-an ká lọ mú ọpọlọpọ àwọn ara wúm di ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí.KameọdúnKamẹrúùn..
wikipedia
yo