cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Èyí tẹ̀síwájú fún ìgbà pípẹ́ kan-fìn-kése títí di àsìkò tí ìjọba àpapọ̀ àgbáyé gbìmọ̀ pọ̀ tí òpin sì òwò ẹrú yìí..
wikipedia
yo
Fún ìdí eléyìí, ó di ọ̀ranyàn kí á dá àwọn ẹrú wọnyi pada sí ibi tí wọ́n ti ṣe wá..
wikipedia
yo
Eyi lo mu ki ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹni ti wọn jẹ ọmọ bibi ilẹ̀ Yorùbá padà si ilé wọn..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ní ọwọ́ àsìkò tí wọ́n fi wà ní oko ẹrú yìí ni wọ́n ti ń ṣe ẹ̀sìn jíjẹ́-ọmọ-lẹ́yìn-kírísítì (Chiristanity) àwọn òyìnbó àṣíṣẹ́sin yìí sì rí i ní ọ̀ranyàn pẹ̀lú láti ṣe agbára lórí i bí ẹ̀sìn yí yóò ṣe máa tẹ̀síwájú láàrín wọn..
wikipedia
yo
Èyí gan-an ló mú kí wọ́n ṣe akitiyan lórí bí wọ́n yóò ṣe ṣe ayiṣe ìwé-mímọ́ ní -Bíbélì sí èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Nínú sí ṣe eléyìí ó ṣe pàtàkì láti rí i dájú pé ọmọ bíbí ilẹ̀ Yorùbá tó sì jẹ́ gbẹ̀dẹ̀-ìjọ èdè náà wà ní bẹ̀ àti kí ó sì kó ipa takuntakun nínú sí sí àyẹ̀wò, àfikún, àfinìyàn, àti àfọ̀ìwádìímá tó yáarántí lọ rí iṣẹ́ náà..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn bíi humnah Kilham (1891) John Ghámì, Gollmer and Bowdich (1817) àti Àjàyí growther (1815) lọ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ lórí kí kó lẹ́tà àti àwọn ònkà jọ.Ọkùnrin kan tí ń jẹ́ Bowdich ni ẹni akọkọ tí o kókó ṣi ṣe lórí i àwọn ònkà Yorùbá bí i, oó, eéjì, ẹẹ́ta títíó do ri i èéwá-a o sì ṣe àwọn iṣẹ́ yìí í ní ọdún (1817)..
wikipedia
yo
Kmah Kilhar ni (1828) náà ṣiṣẹ́ lórí kikó sì lé èdè tí a ń ṣàè bá yìí..
wikipedia
yo
Ó fún wa ní ìlànà meji tí ó ṣe pataki jù ninu iṣẹ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn Crowther, a ò gbọdọ̀ gbàgbé àwọn Dukan-yeekan bi, Henny Venn (Ijo CMS), àlùfáà Charle Andrew Gollmer (German), alufa Sotites..
wikipedia
yo
ti wọ́n ṣe àkànṣe iṣẹ́ takun-takun lórí bí èdè Yorùbá ṣe di ki kó ṣẹlẹ̀..
wikipedia
yo
Àkíyèsí pàtàkì kan ti a lée ṣe nínú gbogbo atótónu lórí bí èdè Yorùbá ṣe di kíkọ́ sílẹ̀ yín í pé nínú gbogbo àwọn tó ṣiṣẹ́ yí tí wọ́n jẹ́ àwọn Òyìnbó àtohun Adékàọ̀kan aláwọ̀ dúdú kan ni a tìmẹ́nu bà, ṣùgbọ́n èyí kò fi bẹ́ẹ̀ rí bẹ̃..
wikipedia
yo
Àwọn dúdú tí wọ́n kó pa nínú iṣẹ́ yìí náà pọ̀ jọjọ ṣùgbọ́n fún ìdí kan tàbí òmíràn tí a kò ní lée sọ̀rọ̀ nípa wọn..
wikipedia
yo
Ìwọ̀nba kéréje tí a lè mẹ́nu bà nínú ìtàn bí èdè Yorùbá ṣe di kíkọ sílẹ̀ ní yí...
wikipedia
yo
Ayan (Wíbu)Iṣẹ́ Aya ìlù lílù ni à ń pè ní iṣé àkẹ̀, àwọn tí ó ń ṣe iṣé yìí ni à ń pè ní "Àlá tàbí ‘Ayanọ̀gágun
wikipedia
yo
Gbogbo ọmọ ti onílù bá bí sí ìdí àyàn àgalù ni ó ní láti kọ́ ìlù lílù, pàápàá àkọ́bí onílù..
wikipedia
yo
Dandan ni kí àkọ́bí onílù kọ́ iṣẹ́ ìlú, kò sì máa ṣe é nítorí àwọn onílù kò fẹ́ kí iṣẹ́ náà parun..
wikipedia
yo
Yàtọ̀ sí àwọn tí a bí ní ìdílé onílù tàbí àwọn ó ọmọdé tí a mú wọ agbo Ifá, Ọbàtálá, eégún tàbí Ṣàngó tí wọ́n sì ń tì pa bẹ́ẹ̀ mọ́ oríṣìíríṣìí ìlú wọn a máa ń rí àwọn tó ti ìdílé mìíràn wá láti kọ́ ìlú lílù lọ́wọ́ àwọn onílù..
wikipedia
yo
Àwọn Yorùbá bọ̀ wọ́n ní “àtọmọdé dé ibi oró ń wò fínní-fínní, àtàgbà dé ibi oró ń wò rànrán” òwe yìí tọ́ka sí i pé kò sí ohun tí a fi ọmọdé kọ tí a sì dàgbà sínú rẹ̀ tí a kò ní lè ṣe dáadáa.Láti kékeré làwọn Yorùbá ti ń kọ́ oríṣìíriṣi ìlú lílù..
wikipedia
yo
Nígbà tí ọmọdé bá ti tó ọmọ ọdún mẹ́wàá sí méjìlá ni yóò ti máa bá baba rẹ̀ tí ó jẹ́ onílù lọ òde aré..
wikipedia
yo
Láti kékeré yìí wá ni yóò ti máa fọ́jú àti ọ̀kan sí bi a ti n lu ìlù..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọdékùnrin tí ń bẹ nínú agbo àwọn tí ń bọ Ọbàtálá yóò máa fojú síi bí a ti ń lu ìgbín, àwọn tí ń bẹ lágbo àwọn onífà yóò máa kọ́ bí a ti ńlu ìpèsè..
wikipedia
yo
Ọ̀nà kan náà yìí làwọn tí ń bẹ lágbo àwọn eléégún àti Oníṣàngó ń gbà kọ́ bí a ti ńlu bàtá..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọdé mìíràn máa ń gbé tó ọdún mẹ́wàá sí mẹ́ẹ̀dógún lẹ́nu iṣẹ́ ìlú kíkọ́ yìí.Yorùbá..
wikipedia
yo
Yàtọ̀ sí ọjọ́ ọdún Ifá, a tún ńlu ìpèsè lọ́jọ́ tí a bá ń ṣe ìsìnkú tàbí ìjáde òkú ọ̀kan nínú àwọn aṣáájú níbi ifá..
wikipedia
yo
Ó sì gbà tó ẹsẹ̀ bàtà tí a fi bò ó lójú mọ́ ara igi tí a gbẹ́ tí a sì dà ihò sínú rẹ̀..
wikipedia
yo
Igi la fi ń gbé afẹ́ré, ṣùgbọ́n ó lẹ́gbẹ́ tí ó fẹ̀ ju ìpèsè kò ga tó ìpèsè, ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta ni ó fi dúró nílẹ̀..
wikipedia
yo
Abala irin méjì tí a papọ̀, ṣùgbọ́n tí a dá ẹnu rẹ̀ sí lápá kan ní agogo.Yorùbá..
wikipedia
yo
Bí ọlọọdẹ tàbí olórí ọdẹ kan bá kú ni a ń lu àgẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọ̀ là fín bóo lójú ọ̀nà méjèèjì, òkun la sì nfi wá awọ ojú rẹ̀ lọ́nà méjèèjì kí ó lè dùn..
wikipedia
yo
Igi la fi gbèé, ṣùgbọ́n kò ga, kò sì fẹ́ lẹ́nu tó afẹ́rẹ̀..
wikipedia
yo
Bi oba ba gbese tabi ijoye nla kan tẹ́rí gbaṣọ wọn n lu gbẹ̀du lati fi túfọ̀.Awon itọkasi asa Yoruba..
wikipedia
yo
Ìlú ìgbdakálú òrìṣà Ọbàtálá ní ìlú yìí ọjọ́ àjọ̀dún Ọbàtálá ní àwọn ọlòyín yìí nkó ijó ìgbín sóde..
wikipedia
yo
Oríṣìí ilu mẹrin la le tọka si lábẹ́ òwò ìgbín..
wikipedia
yo
Awon ti n gbe ilu yii maa n ṣoju ati imu sára igi ilu yii.Yorùbá..
wikipedia
yo
Ṣugbọn gbogbo ohun ti iṣaaju ni náà ni kànnàǹgó ni..
wikipedia
yo
Bí a bá tẹ kóńgò bọ kànnàǹgó, ó ń dún létí KÈRÉKÈRÉ ju ìṣáájú.Yorùbá..
wikipedia
yo
Gùdùgudu ìlú yí gan an là bá máa pè ní omele dùndún..
wikipedia
yo
Ó fi èyí yàtọ̀ sí àwọn bí ìyá-ìlú, kẹríkẹrì, gangan, ìṣáájú àti kànnàǹgó tí wọ́n ní ojú méjìméjì..
wikipedia
yo
Ìlú yìí kò ṣe gbé ko apá bí ti àwọn yòókù ọ̀run la máa ń gbé e kọ́ nígbà tí a bá ń lùú..
wikipedia
yo
BÍ Ó TI kéré tó ipa tí ó ń kó nínú ìlú bọ́ọ̀lù kò kéré..
wikipedia
yo
Kẹ̀rẹ̀kẹ̀rẹ̀ ní ń dùn nígbà gbogbo nítorí pé awò ojú ilú náà kò dé rárá.Àwọn ìtọ́kasí àṣà Yorùbá..
wikipedia
yo
Dísẹ̀ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun èlò amúlùúdùn ní ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
jákè jádò ilẹ̀ Yorùbá la ti n lú ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀, pàá pàá jùlọ níbi àṣeyẹ oríṣiríṣi.”ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀" jẹ́ ọ̀kan..
wikipedia
yo
Lára oh ún tí ó ń mú ìdàgbàsókè ìdàgbàsókè àti ídánisí fún àwọn ènìyàn ní àwùjọ . Díkẹrẹ yí ọ̀kan lára ohun ìlú tí wọ́n ti ń loni apá ìwọ̀ Oòrùn nd orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí a so ìlẹ̀kẹ̀ mọ́ lára ìgbà tí a sì fi àwọn ṣọ́ ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ jẹ́ irinṣẹ́ ìlú tí ó wọ́pọ̀ niìwọ oòrùn Áfíríkà àti láàárín àwọn aláwọ̀ funfun..
wikipedia
yo
nígbàtí a bá n kọrin ni a máa n míì.Oríṣiríṣi ọ̀nà ni àwọn ìlú kànkàm ń pè ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ ìlú Cuba ń pèé ní "Chekéré” wọ́n sì tún pèé ní "AGgue(ABW)..
wikipedia
yo
ó sì tóbi lórí níbi tí a fi awọ bò ju ìsàlẹ̀ lọ, ó ní ọ̀já tẹ́ẹ́rẹ́ tí a lè fi gbé e kọ́ apá..
wikipedia
yo
Awọ tẹ́ẹ́rẹ́ bí okùn ṣòkòtò yí náà ni wọ́n fi má ń fà tí wọ́n sì ń fọwọ́ kan ojú ìlú náà kí ọ̀lẹ mú ohun tí onílù náà bá fẹ́ jáde lásìkò tí ó bá ń lùú..
wikipedia
yo
Irin la fi ń ṣe aro, àwọn alágbẹ̀dẹ ló sì ń ṣe é.Àwọn ìtọ́kasíàṣà Yorùbá..
wikipedia
yo
Ó yàtọ̀ sí ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ tí a kọ́kọ́ ṣàlàyé rẹ̀ nítorí pé a kìí lu aro, Koṣọ́, ati bẹ̀m̀bẹ́ síi..
wikipedia
yo
Bí a bá ti sẹ́ẹtán, a ó fi òwú tí a ṣe èso sì yí kó ara àgbẹ̀ náà lọ́wọ̀ọ̀wọ́ títí dé ọrùn rẹ̀..
wikipedia
yo
Èso ara àgbẹ̀ yí ní ń dùn lára rẹ̀ nígbà tí a bá ń lùú..
wikipedia
yo
Àgbẹ̀ tí a fi ń ṣe Emelé-àjẹ́ kò tóbi tó èyí tí a fi n ṣe ìyà-àjẹ́..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí dídún wọn kò fi fẹ́ dòdò bi ti Olówó-Ajé.Yorùbá..
wikipedia
yo
BWA tàbí Bjìyà (lopo) jẹ́ ẹ̀yà kan ní àrin ilé the places left unínìn were raidẹd by the bamana, which led to a Weakẹning of the be social and political systems..
wikipedia
yo
iye àwọn ènìyàn ẹ̀yà yĩ jẹ́ jẹ́ 300,000 lápapọ̀.itotolákọsílẹ̀kánkányailrikafrika..
wikipedia
yo
Ìran àwọn tí ó ń sọ èdè yìí wà ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Congo àti Portuguese..
wikipedia
yo
Àwọn alabagbée wọn ní Luba-Lunda.Orílẹ̀ èdè Angola ni a ti ń sọ èdè yìí..
wikipedia
yo
Lara ebi Niger-gg0 ni ede yii wa, ẹka rẹ si ni Bantu.Afrika..
wikipedia
yo
Gúṣù ila Oòrùn Orílẹ̀ Èdè Nigeria ni wọ́n tí ń sọ èdè yìí..
wikipedia
yo
Ẹ̀yà àwọn tí ó ń sọ èdè Ibibio ni wọ́n, wọ́ wa ní ìpínlẹ̀ Akwa-Ibom ní orílẹ̀ èdè Nigeria..
wikipedia
yo
Odò Kongóorilẹ̀-èdè Olómìnira Ilẹ̀ Kongóorilẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóńgò..
wikipedia
yo
gbogbo àwọn èdè náà ni wọ́n sì ti ń sọ títí di àkókò yìí..
wikipedia
yo
Àwọn Niger-Congo tó jẹ́ ẹ̀yà bíjagọ̀ ló máa ń sọ èdè náà.Afrika..
wikipedia
yo
Olówó Madarébo Madarẹ̀ yìí jẹ mọ́ èyí tí wọ́n máa ń sọ ní ìwọ̀ oòrùn Africa..
wikipedia
yo
Àwọn èdè àdúgbò wọn ní Bengé Olówó, Dives bọbọ, kíkọ̀ àgbọ́kìré yaya yabẹ̀rẹ̀ vọ̀rẹ́ ìṣeùn..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n síjẹ̀ ẹyẹ ti Niger-Congo pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà bọ̀bọ́..
wikipedia
yo
Wọ́n sì ti ń sọ àwọn èdè wọ̀nyí títí di oní.Afrika..
wikipedia
yo
Busọògì (bushọg)bush bushg ni a mọ èdè yìí sí..
wikipedia
yo
Ripong, Bushong, BushoNGO, buong, Ganga, Kuba Mbale, ngongo shoNGO..
wikipedia
yo
Wọ́n jẹ mọ́ ẹ̀ka èdè ti ddenbẹ, Ngéńdé, NGO. SI28, NGOSISI, Panga, pianga, Shoba, Shobuia isowa..
wikipedia
yo
Èdè náà ti wà títí di òní lápá ìjọba Onímíra ilẹ̀ Congo..
wikipedia
yo
Bákan náà ni wọ́n jẹ́ ẹbí Niger-Congo ní ọwọ́ ti Bushong..
wikipedia
yo
Èdè Idomaa le ri Idoma ni aarin gùngùn orílẹ̀ èdè naigiria..
wikipedia
yo
Àwọn tí wọn ń sọ èdè yìí jẹ́ ìgbà meji ati aadọta ẹgbẹrun..
wikipedia
yo
Àwọn aládúgbòò rẹ̀ ní Ibibo, igbo, màmá àti múmúyè..
wikipedia
yo
wọ́n sì máa ń ṣe àpọ́nlé àwọn baba ńlá wọn tí wọ́n ti kú.Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Músùn wọ̀nyí jẹ́ ara ènìyàn Nàìjíríà, wọ́n kéré níye, wọ́n sì dá dúró tẹ̀lé ni..
wikipedia
yo
Asa Nok yo jade ni arin ile Naijiria ni bi odun 1000 kede o si parẹ lai nidi ni bi odun 200 lk..
wikipedia
yo
A kò mọ ohun tí àwọn eniyan náà pe ara wọn, nítorí náà orúkọ àṣà náà ni wọ́n fi sọ ìlú wọn..
wikipedia
yo
Àsá nok wa lati ariwa Afrika ni IpinleNiger.signi The Noorílẹ̀Aráls Ilels Naijiria..
wikipedia
yo
Èdè igbira tàbí Èbìrà tàbí Egbra jẹ́ èdè ni Nàìjíríà (ni àwọn ìpínlẹ̀ Kwara àti ẹ̀dọ̀ àti Nasarawa)..
wikipedia
yo
Èdè igbira Èdè yìí jẹ ọ̀kan lára àwọn èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n wà ní agbègbè Èbìrà ní ìpínlẹ̀ kogi, kwara, ẹ̀dọ̀, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Awon eka ede ti o wa ni abe re ni Okene (hima, Hhima) ìgbá (ẹ̀tunno) Èbìrà ní iṣupọ ẹ̀ka èdè, wọ́n ń lò ó ní ilé ìwé.Awon ìtọ́kasí̀ àwọn èdè Nàìjírípínlẹ̀ Kwara Kipinle Eyowaayo kukuru kukuru..
wikipedia
yo
Ipinnu tabi Èbìrà jẹ́ ẹ̀yà eniyan ni Nàìjíríà.Èdè yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n wà ní agbègbè Èbìrà ní ìpínlẹ̀ Kwara, ẹ̀dọ̀, Okene àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Awon eka ede ti o wa ni abe re ni Okene (hima, Hhi) gbára (ẹ̀tunno) Èbìrà ní iṣupo ẹ̀ka èdè, wọ́n ń lò ó ní ilé ìwé.Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Kọ́ọèdè kọInorúkọ àdúgbò tí wọ́n ń pè é ní itajìkàn..
wikipedia
yo
Àwọn mọ̀lẹ́bí èdè kòin ní Niger-Congo, Atlantic-Congo, Volta-Congo àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ...
wikipedia
yo
KíNGO tàbí èdè kóńgò jẹ́ èdè Bantu tí àwọn ẹ̀yà bánkọ àti Banmọ́sì ń sọ.A tí àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń sọ ní kí kímba, oun ta ń pe ní nkonko ní ń nkan ṣe pẹ̀lú àpapọ̀ àwọn èdè Bantu..
wikipedia
yo
Ní àárín ọdún (1960) sí ọdún (1996) àwọn tí ó ń sọ èdè yìí dín díẹ̀ ní mílíọ̀nù mọ́kànlá..
wikipedia
yo
Àkọtọ́ èdè wọn múná dóko; ṣùgbọ́n wọn kìí lo àmì ọ̀hún lórí gbogbo ọ̀rọ̀ wọn..
wikipedia
yo
Àkọtọ́ wọn tó wuyì yìí ló mú kí ohun èdè wọn dín kù ní lílo.Ológun Kóńgòró tàbí KíkóNGO - ò jẹ́ èdè Bantu, àwọn ènìyàn nkorẹ́ ni wọ́n ń sọ ọ́..
wikipedia
yo
Àwọn tí wọ́n ń sọ ọ́ jẹ́ mílíọ́nù méje ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí wọ́n kọ́ ní ẹrú ní ilẹ̀ àyé tí wọ́n sì ta wọ́n fún America ni wọ́n ń sọ èdè yìí..
wikipedia
yo
Àwọn bí i mílíọ́nù ni wọ́n ń lo èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè méjì.Kóńgò language..
wikipedia
yo
Akande titilayo C.síntáàsì èdè Aladẹtyl- John R..
wikipedia
yo
Watters túmọ̀ sinǹtáá sí bí ìró àti ọ̀rọ̀ ṣe ń sọ papọ̀ di gbólóhùn, àti bí àwọn ìsọ̀rí kọ̀ọ̀kan ṣe hun ara wọn papọ̀ ní ìpele, ìpele di gbólóhùn.Gbogbo èdè ni wọ́n ní ju ọ̀nà kan lọ tí wọ́n ń gbà hun ọ̀rọ̀ wọn..
wikipedia
yo
Tí a bá ń kọ nípa èdè kan, àfojúsùn wa ni láti ṣe àfiwé ìdí tí ìhun wọn fi pe oríṣìíríṣìí..
wikipedia
yo