cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Nígbà tí a sì rí Cross River ní abẹ́ Banòrùn-Cross..
wikipedia
yo
Ní ìparí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀mọ̀wé ni wọ́n ti ṣe iṣẹ́ ìwádìí lórí rẹ̀ ṣùgbọ́n ààyè ṣì tún ṣí sílẹ̀ fún àwọn ìpẹ́ẹ̀rẹ̀ tulẹ̀ láti ṣe iṣẹ́ ìwádìí àti lámèyítọ́ lórí ẹ̀ka èdè Niger-Congo.Àwọn èdèAfrika..
wikipedia
yo
Mangbétúàwọn ènìyàn yìí wà ní abala àríwá Congo, wọ́n sì tó òkè méjì ní iye..
wikipedia
yo
Èdè mangbetuti ni wọ́n ń sọ, wọ́n sì múlé gbe àwọn Azan, mbutí àti Momvuvu..
wikipedia
yo
Ó jọ pé orílẹ̀ èdè sundán ni wọ́n ti ṣe wá; àgbẹ̀, òde àti apẹja sì ni wọ́n..
wikipedia
yo
Òrìṣà Klimá tàbí nọ̀rọ̀ ni wọ́n ń bọ gẹ́gẹ́ bí Ẹlẹ́dàá, wọ́n a sì máa bọ ara náà.Afrika..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà yìí wà ní orílẹ̀ èdè Congo, Zambia àti Angola, èdè wọn sì jẹ́ ẹ̀yà ti Bantu..
wikipedia
yo
Wọ́n dín díẹ̀ ní ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án wọ́n sì múlé gbe ẹ̀yà yakà, ṣúku, Chókwè abbl..
wikipedia
yo
A rí àgbẹ̀, apẹja àti oníṣòwò tààrà ní orílẹ̀ èdè yìí..
wikipedia
yo
baálẹ̀ kọ̀ọ̀kan náà sì sá ṣùgbọ́n ìṣákọ́lẹ̀ pọn dandan..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń dífá alágbọ̀n ṣùgbọ́n wọ́n gbàgbọ́ nínú nZambi.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Lusiwaoluwakunibajade eniyan yii to bii oke kan ni iye, ẹya ede Bantu si ni won n so..
wikipedia
yo
Àdúgbò Congo ni wọ́n wà, wọ́n sì múlé gbe Salakasú, Mbagani, kété, Lunda,dá, Luba àti Chókwè..
wikipedia
yo
Wọn a máa ṣe àgbẹ̀ àti ọdẹ wọn a sì máa ṣe iṣẹ́ ọnà..
wikipedia
yo
Wọ́n ní ìgbàgbòn nínú Olódùmarè (MV mùkúlú) àti ẹlẹ́dàá (Nláárí) ṣùgbọ́n wọ́n máa ń wárí fún àwọn alálẹ̀...
wikipedia
yo
Wọ́n wà ní àdúgbò orílẹ̀ èdè Tanzania àti Kenya, wọ́n sì fẹ́ẹ̀ tó ọ̀kẹ́ mẹ́tàdínlógún ààbọ̀ ní iye..
wikipedia
yo
Èdè wọn ni òì máa wọ́n sì mulẹ̀ gbe Samburu, Kikuyu, Kamma, Chaga, Meru abbl..
wikipedia
yo
Ọjọ́ orí ni wọ́n máa fi ń ṣe ìjọba ní ilẹ̀ yìí, obinrin wọn kìí sìí pẹ́ ní ọkọ ṣugbọn ọkunrin gbọdọ̀ ní owó lọ́wọ́ kí ó tó fẹ́ aya..
wikipedia
yo
Ní àsìkò ayẹyẹ pàtàkì, màálù ni wọ́n máa ń fi rúbọ.Afrika..
wikipedia
yo
MahaKọ́múníìsìÀwọn ènìyàn yìí lé ní mílíọ̀nù kan àti ààbọ̀, wọ́n ń gbé ní apá gúúsù ìwọ̀ oòrùn Madagascar..
wikipedia
yo
Àgbẹ̀ àti darandaran sì ni wọ́n; wọ́n gbajú gbajà fún fínfín àti kíkun ibojì/sàréè..
wikipedia
yo
Wọ́n ní ìgbàgbọ́ nínú òrìṣà àkúnlẹ̀bọ, aṣòdì sí ẹ̀kọ́ Kristiẹni ni ìjọba wọn tẹ́lẹ̀, wọn kò ní àǹfààní lati gbọ nípa orúkọ Jesu..
wikipedia
yo
Nísisìyí ẹ̀sìn òmìnira ti wà ṣùgbọ́n ojú ọ̀nà tí kò dára n pa ìtànkalẹ̀ ìhìnrere lára.Afrika..
wikipedia
yo
Makondéédé Bantu ni wọ́n ń ṣọ́, wọ́n sì wà ní Tanzania àti Mozambique..
wikipedia
yo
Àwọn Mwéra, Makua ati Mábíà ní àwọn alámùúlégbè wọn..
wikipedia
yo
Abúlé kọ̀ọ̀kan ni ó sì ní baálé tirẹ̀, àwọn alálẹ̀ ni wọ́n sì máa ń bọ́ bíi Ọlọrun ti wọn.Afrika..
wikipedia
yo
Mambì àwọn ènìyàn yìí wà ni orilẹ-ede Naijiria ati Kamẹrúùnù, wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n, wọ́n sì mulẹ̀ tí àwọn ènìyàn bíi kàkà, tíkòng àti báfúm..
wikipedia
yo
ẹ̀sin Musulumi àti ti ìbílẹ̀ ni wọ́n ń ṣe papọ̀.Àwọn wọ̀nyí wà ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Kamẹrúùnù..
wikipedia
yo
ẹ̀sìn ìbílẹ̀ àti ẹ̀sìn mùsùlùmí ni wọ́n n sin.Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Murtala Ramat Mohammed ti a bi ni November 8, 1938-February 13, 1976)jẹ Olórí Ìjọba Nigeria gẹ́gẹ́ bí ológun lati ọdún 1975 si 1976..
wikipedia
yo
Ìgbà tí àwọn ológun ẹgbẹ́ rẹ̀ fẹ́ gba ìjọba ni wọ́n pa..
wikipedia
yo
Ọ̀gágun Ọbásanjọ́ tí ó jẹ́ igbákejì rẹ̀ ni ó bọ́ sí orí oyè gègé olórí ìjọba láti 1976 sí 1979.Ìgbésí ayéa bí ọ̀gágun Murtala Ramat Muhammed ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù kejì ọdún 1938 (8/2/1938)..
wikipedia
yo
O di alakoso ologun orile ede Naigiria ni 1975 titi di odun Feb 13, 1976 Murtala Mohammed je ẹlẹṣin Musulumi, Hausa ni pẹlu lati (oke oya apa guusu..
wikipedia
yo
O keko ologun ni British Academy, Sẹ̀sanhurst ko faramọ Ijoba Ologun Johnson Aguiyi Ironsi ti o fipa gba joba ni osu kìíní odun 1966 ninu eyi ti won pa ọpọlọpọ olori Naijiria to je omo apa guusu lona to buru jáì! fun idi eyi o kopa ninu ìfipá - gba ijoba to waye ni July 21, 1966..
wikipedia
yo
Wọ́n fipá gba pápákọ̀ òfúrufú Ìkẹjà; èyí ti wọ́n ti yí orúkọ rẹ sí Murtala Mohammed International Airport lati fi yẹ..
wikipedia
yo
O kọ́kọ́ fẹ́ fi ìfipá gba ìjọba yìí gẹ́gẹ́ bíi ìgbésẹ̀ fún àwọn ará gúúsù láti yà kúrò lára Nàìjíríà ṣùgbọ́n o da àbá yìí nù nígbẹ̀yìn.Ìfipá gbàjọba yìí ló mú Ọ̀gágun (Lieutenant-Colonel) Yakubu Gowon jẹ́ Alakoso orílẹ̀ èdè Naigiria..
wikipedia
yo
Ní July/29/1975 Àwọn ológun tó jẹ́ ọ̀dọ́fi Ọ̀gágun Murtala jẹ́ Alakoso orílẹ̀ èdè yìí láti jẹ́ kí naigiria padà sí ìjọba Alágbádá Democracy..
wikipedia
yo
Ọmọ ọdun mejidinlogoji ni Murtala Ramat Muhammed nigba ti awọn ologun fi jẹ alakoso rọpo Gowon..
wikipedia
yo
O jẹ ọkan ninu adari ọmọ ogun naigiria nigba ti ogun naa doju ina tan po..
wikipedia
yo
Òun ló fà á ti ìkọjá Odò Ọya (River Niger) àwọn ọmọ Ogun Ribiya Biafra ṣe já sí pàbó..
wikipedia
yo
Murtala ò lọ́wọ́ sí bí ìfipá-gbà-jọba tó mú gorí oyè.Lọ́gán tí Murtala gbàjọba, ara ohun tó kọ́kọ́ ṣe ni; ó pa ètò ìkànì [[Census]] ti ọdún 1973 rẹ̀, eléyìí tó jẹ́ pé ó fi jù sí ọ̀dọ̀ àwọn gúúsù nípa ti àǹfàní..
wikipedia
yo
Ó padà sí ti ọdún 1963 fún lílò nínú iṣẹ́.Murtala Mohammed yo ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀gá iṣẹ́ ìjọba tí ó ti wà níbẹ̀ láti ìgbà Ìjọba Gowon..
wikipedia
yo
O tun mu ki awọn ara ilu ni igbẹkẹle ninu ijọba alápapọ̀..
wikipedia
yo
Ó lé ní ẹgbaarun (10,000) òṣìṣẹ́ ìjọba ti Murtala yọ lẹ́nu iṣẹ́ nítorí aiṣootọ lẹ́nu iṣẹ́, àbẹ̀tẹ́lẹ̀, Jegudu-jẹra, ṣíṣe ohun ìní ìjọba báṣubàṣu, àìlèṣiṣẹ́-lọ́nà-tó yẹ tabi ọjọ́ orí láìfún wọn ní nkankan..
wikipedia
yo
Fífọmọ Murtala kan gbogbo iṣẹ́ ìjọba pátápátá, bí àwọn ọlọ́pàá, amòfin, Ìgbìmọ̀ Tó Ń mójútó Ètò Ìlera, Ológun, àti Adékíadé..
wikipedia
yo
Àwọn olórí iṣẹ́ ìjọba kan ni wọ́n tún fi ẹ̀sùn jẹgudu jẹra kan, tí wọ́n sì báwọn dé ilé ẹjọ́..
wikipedia
yo
O fun awọn Alágbádá ni mejila ninu ipo mẹẹdọgbọn ti amojuto igbimọ iṣe ijọba..
wikipedia
yo
Ìjọba àpapọ̀ gba àkọ́so ilẹ̀ iṣẹ́ ìròyìn méjì tí ó tóbi jù lọ lórílẹ̀ èdè yìí..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ kí gbígbé ìròyìn jáde wà lábẹ́ ìjọba àpapọ̀ nìkan..
wikipedia
yo
Murtala mu gbogbo Yunifasiti to wa labẹ ijọba ipinlẹ si abẹ́ akoso ijọba apapọ.Mélòó Stephanie ka ninu ẹ̀yìn Adepẹlẹ ni ọrọ awọn ohun ribi-ribi ti Murtala Gbèsè nigba ti re..
wikipedia
yo
Ara wọn tún ni dídá ìpínlẹ̀ meje mọ́ mejila tó wà tẹ́lẹ̀ láti di mọkandinlogun..
wikipedia
yo
Murtala ṣe àtúnyẹ̀wò ètò ìdàgbàsókè ẹlẹ́kẹta Orílẹ̀ èdè..
wikipedia
yo
Ó rí ìgbọ́wọ́lórí (Inflation) gẹ́gẹ́ bí ìdàmú ńlá tó ń ṣe jàm̀bá fún ọrọ̀ ajé ẹ wà..
wikipedia
yo
Fún ìdí èyí, ó pinnu láti dín owó tó wà lóde pàápàá èyí tí wọ́n ń ná lé iṣẹ́ ìjọba lórí kù..
wikipedia
yo
O tun gba awọn oníṣẹ́ àdáni níyànjú láti máa ṣẹ̀ṣẹ̀ ti àwọn òṣìṣẹ́ gbogbo-ò-gbọ́ ti jẹ gàba lé lórí..
wikipedia
yo
Murtala tun ṣe atunyẹwo oye iṣẹ itọju ilu to ni ṣe pẹlu ilu miiran ti awọn ẹgbẹ ilu ti o n ṣẹda epo rọ̀bì ọdun (OPEC)..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ kí Nàìjíríà jẹ́ ohun kìíní tí ó kà sí nípa ti ànfàní àti iye tí wọ́n dalẹ̀ epo rọ̀bì.láìrò tẹ́lẹ̀, Ọ̀gágun Murtala dèrò ọ̀run ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejì, ọdún 1976..
wikipedia
yo
Wọ́n dá lọ́nà nínú mọ́tò rẹ̀, nígbà tí oun ti mọ́ṣáláṣí bọ̀ nínú ìfipá-gbà-jọba tí ó jẹ́ ìjákulẹ̀ nígbẹ̀yìn..
wikipedia
yo
Ọwọ́ tẹ àwọn ọlọ̀tẹ̀ tó pa á, ṣùgbọ́n kí lẹ tó pa òṣìkà ohun rere a ti bà jẹ́..
wikipedia
yo
ká tó rẹrìn ó dìgbò, ká tó rẹ̀fọ́n ò do dan, ká tó Reye bi Oọ̀kín Murtala Ramat Mohammed ìyẹn di gbére.Ìtọ́kasí àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Muhammadu Buhari (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù kejìlá ọdún 1942) olóṣèlú tí ó jẹ́ Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láàrín ọdún 2015 sí ọdún 2023..
wikipedia
yo
Ó lọ sáà àkókò rẹ̀ láàrin ọdún 2015 sí 2019 àti kejì láàrín ọdún 2019 sí 2023..
wikipedia
yo
Buhari ti fìgbà kan jẹ́ ọ̀gágun mẹ́jọ genera àti pé ó jẹ́ olórí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti 31st oṣù Kejìlá ọdún 1983 sí oṣù kẹjọ Ọdún 1985, lẹ́yìn tí ó fi kúupù ológun gbàjọba.Ìgbésí ayé tètèá bí Muhammadu Buhari sí ìdílé Fúlàní ní ọjọ́ 17 Kejìlá 1942, ní Daúura, ìpínlẹ̀ Kat, bàbá rẹ̀ ni Hardo Adamu, ẹni tí ó jẹ́ olórí Fúlàní, orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni Zuhat, ẹni tí ó Hausa..
wikipedia
yo
Ìyà Buhari ni ó tọ́ dàgbà, baba rẹ̀ fi ayé sílẹ̀ nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rinrìn.Ìgbésí ayé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ológunBuhari dára pọ̀ mọ́ Nigerian military Training College (N-pìta) ní ọdún 1962, ó jẹ́ ọmọ ọdún kan dínlógún nígbà náà..
wikipedia
yo
Ní oṣù kejì ọdún 1964, a yí orúkọ ilé-ìwé ológun náà padà sí Nigerian defence Academy (ńdá)..
wikipedia
yo
Ní àárín 1962 sí 1963, Buhari kọ́ nípa ìmọ̀ ogun ní mons Officer çt School ní Ìlú Aldershot, England..
wikipedia
yo
Ni osu kinni odun 1963, nigba ti Buhari je omo odun ogun, a so di gùnTenanti keji.Awon itọkasiawon Aare ile Naijirimeje ogagun ara Naijiria..
wikipedia
yo
Chuba ọkàdìgbò (17 December, 1941 – 25 September, 2003) jẹ oloselu ọmọ ile Naijiria lati ẹya Igbo ti a bi ni ọdun 1941 ti o si ku ni ọdun 2003..
wikipedia
yo
ọkàdìgbò jẹ́ ààrẹ àwọn alàgbà ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Nàìjíríà láti 1999 títí dé 2000.Ìtọ́kasíàwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oríṣìíríṣìí àwọn onímọ̀ ni ó ti gbìnyanjú láti fún èdè ní oríkì kan tàbí òmíràn, ṣùgbọ́n kí a tó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn oríkì wọ̀nyìí, kí èdè túmọ̀ sí? Èdè níí ṣe pẹ̀lú ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò ní àwùjọ yálà fún ìpolówó ọjà, ìbaráẹní sọ̀rọ̀ ojoojúmọ́, ètò ìdílé tàbí mọ̀lẹ́bí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Ohun tó fà á ni pé èdè kọ̀ọ̀kan ló ní ìwọ̀nba irú tó ń mú lọ..
wikipedia
yo
5.Kókó ni a ń kọ́ ọ, kì í ṣe àmútọ̀runwá 6.Nǹkan ẹlẹ́mu-ín tó lè dàgbà sí i, tó sì lè kú ikú àìtọ́jọ́ ní èdè..
wikipedia
yo
Síwájú sí i, a ní àwọn àbùdá ti èdè ènìyàn gẹ́gẹ́ bí àwọn onímọ̀ ṣe ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ (1)Idohu yàtọ̀ sí ìtumọ̀ (ar'billion ) (2] asa (cultural transmission) (3)agbára ìbísí (ọpẹ́dvity) àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Gbogbo ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ mìíràn yàtọ̀ láàrín èdè ènìyàn àti ti ẹranko kì í ṣe ohun tí ó rọrùn rárá..
wikipedia
yo
Nǹkan àkọ́kọ́ niyà ẹ a gbọ́dọ̀ wá oríkì èdè tó ń ṣiṣẹ́ lórí èyí tí a ó gbé ìpínlẹ̀ àfiwé wa lé..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ṣá, kò sí oríkì tí ó dàbí ẹni pé ó ṣàlàyé oríkì èdè tàbí tí ó jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà fún gbogbo ènìyàn..
wikipedia
yo
Torí náà, a lè pinu bóyá èdè ẹranko pàápàá ni àwọn Abida yìí pẹ̀lú…ohun tí a mọ̀ nípa èdè ẹranko ni pé, kò sọ èdè ẹranko kọ̀ọ̀kan tí ó ní àwọn àbùdá èdè ènìyàn tí a ti sọ síwájú..
wikipedia
yo
Èyí ni ó mú kí a fẹnukò wípé àwọn ẹ̀dá tí kìí ṣe àwọn ènìyàn kì í lo èdè..
wikipedia
yo
Dípò èdè, wọ́n á máa bá ara win sọ̀rọ̀ ní ọ̀nà tí ń pè ní ẹnà, àpẹẹrẹ ifiyesi (signal cocle).Gbogbo ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ mìíràn yàtọ̀ sí èyí kì í ṣe èdè..
wikipedia
yo
Gbogbo ariwo tí a ka sílẹ̀ wọ̀nyí kì í ṣe èdè nítorí pé; (1)wọn kò ṣe é fọ́ sí wẹ́wẹ́ (2)wọn kì í yí padà (3)wọn kì í sì í ní ìtumọ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn nǹkan tí mo ti sọ nípa ìyàtọ̀ tó wà láàrín èdè ènìyàn àti ẹranko, ó hàn gbangba wípé a kò le è fi èdè ẹranko àti ti ènìyàn wẹ ara wọn..
wikipedia
yo
Yorùbá bi wọn ni “Igi imú jinà si ojú, bẹ́ẹ̀ a ko leè fi ikú wé oorun..
wikipedia
yo
Nínú èdè ènìyàn láti rí gbólóhùn tí ènìyàn sọ jáde tí a sì lée fi ìmọ̀ ẹ̀dá èdè fọ́ sí wẹ́wẹ́..
wikipedia
yo
Atiwipe anfani kakà ede lu ede ko si ni awujo eranko gege bi i ti eniyan..
wikipedia
yo
Olù ra iṣu olú nínú gbólóhùn yìí jẹ́ ọ̀rọ̀-orúkọ ní ipò olúwa, rá jẹ́ ọ̀rọ̀-ìṣe nígbà tí iṣu jẹ́ ọ̀rọ̀ orúkọ ní ipò ààbò..
wikipedia
yo
A kò lè rí àpẹẹrẹ yìí nínú gbígbọ́ ajá, kíkẹ́ ẹyẹ àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Nítorí náà èdè ènìyàn yàtọ̀ sí ẹnà àpẹẹrẹ, ìfiyèsí (jókíl Code) àwọn ẹranko.Àwọn ìwé àmúlò fàtusìn, S.A (2001), An Introduction to the Phonetics and PhoAlágbára of English..
wikipedia
yo
Raji, S.M (1993), ÌTÚPALẸ̀ ÈDÈ asa LÍTÍRÉṢỌ̀ YORÙBÁ
wikipedia
yo
Ogunsiji, a and Akínpẹ̀lú ò (2001), reading in English Languag and Communication Skills..
wikipedia
yo
Nico Cipolone eds (1998), language Files Ohio State University Press, Columbus.ìtọ́ka si..
wikipedia
yo
mẹrinawọní tí wọn n sọ èdè wọnyi jẹ ara madara-yi..
wikipedia
yo
Wọ́n ní ìtàn tó gbọ́orin nípa ìṣẹ̀dá wọn àti nípa àṣà àti ètò òṣèlú wọn láàrín oríṣi àwọn ènìyàn Madagascar..
wikipedia
yo
Ẹ̀yà Oníṣègùna jẹ́ Ẹ̀yà tí ó tóbi ní Áfíríkà Wọ́n Lé ní Òkè Méjìbẹ̀rẹ̀.Ni Group àwọn àgbàn èdè àgbàn ìkórè Syllaba (kíkà-i)..
wikipedia
yo
mossi (tàbí moaaga) àwọn ẹ̀nìyàn mossi jẹ jagunjagun..
wikipedia
yo
Àwọn tó kọ́kọ́ dá mọ̀ssí àkọ́kọ́ sílẹ̀ wá láti gbaná..
wikipedia
yo
Ẹ̀yà ngbaka tàbí M'Bakajẹ́ ẹ̀yà ènìyàn ní orílẹ̀-èdè Olómìnira arin ilẹ̀ Áfríkà.Àwọn wọ̀nyí jẹ́ àwọn tó ń gbé ìlú ngbàkà, kò sì sí agbára kan tó dà wọ́n pọ̀, ńṣe ni olúkúlùkù ń ṣe bí ó ti fẹ́ láàrín ìlú..
wikipedia
yo
Thomas Peter Taiwo seìtàn bí èdè Yorùbá ṣe di kíkọ́ sí le (Yorùbá Orthography)Láti ayébáyé, èdè Yorùbá wà lábẹ́ ìpínsí sórí ti ọ̀gbẹ́ni thamStrong (1964) ṣe fún àwọn èdè gbogbo èdè Yorùbá bọ́ sí abẹ́ ìpín èdè "Kwa"
wikipedia
yo
Èyí sì jẹ́ bẹ́ẹ̀ nítorí pé ède olóhun (bólanguage) ní Yorùbá jẹ́..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí a ṣe mọ̀ pé tẹ́lẹ̀-tẹ́lẹ̀ rí, a kì í kọ́ èdè Yorùbá sí lẹ̀, ṣì sọ nìkan ni à ń sọ ọ́ lẹ́nu..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn Òyìnbó aláwọ̀ funfun dé tí òwò ẹrú sì bẹ̀rẹ̀ ní péré wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ní í kó àwọn ọmọ bíbí ilẹ̀ Yorùbá lẹ́rú lọ sí òkè-òkun..
wikipedia
yo