cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àwọn èdè yìí gbálẹ̀ tààrà ni ilẹ̀ Áfíríkà, wọ́n sì jọra gidi..
wikipedia
yo
Ní abẹ́ gírámà rẹ̀, a ríi wí pé àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ inú àwọn èdè yìí jọra gan-an, èyí ni ó sì mú àwọn onímọ̀ tí ó jẹ́ aláwọ̀ funfun fi ara balẹ̀ ṣe iṣẹ́ ìwádìí ní orí àwọn èdè wọ̀nyí..
wikipedia
yo
Koelle ati Ojúkk so wi pe ọpọlọpọ ẹya ede ti awon eniyan iwo oorun Afirika n so ni o ni oro oruko ti a ṣẹda nipa àfòmọ́ ibẹrẹ..
wikipedia
yo
Nínú ìwádìí tirẹ̀, mẹinini ṣa àwọn èdè kan jọ tí wọ́n fi ara pe ara wọn láti ara ọ̀rọ̀ orúkọ wọn ṣùgbọ́n tí girama wọ́n yàtọ̀ díẹ̀..
wikipedia
yo
Èyí ni òun pè ní ‘semi-Bantu’.man ṣe iṣẹ́ tí ó jọ mọ́ ti mẹinwọ̀n díẹ̀..
wikipedia
yo
Ní tirẹ̀, ó ṣe ìpinyà láàrín àwọn èdè tí ó farahàn ní ìlà-oòrùn àti ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Sudan..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ sílébù nínú àwọn èdè wọ̀nyí ni wọ́n jẹ́ 'CcGreenGreenberg yapa díẹ̀ nínú ẹ̀rọ ti rẹ̀..
wikipedia
yo
O ṣe àtúnpín àwọn èdè wọ̀nyí láàrín ọdún 1949 sí 1954..
wikipedia
yo
Ní tirẹ̀, ó pín Bantu àti ìwọ̀ oòrùn Sudan sí ọ̀nà kan ṣoṣo tí ó pè ní Niger-Congo, ó sì ṣe àdáyanrí ìlà oòrùn Sudan sí ìsọ̀rí mìíràn ọ̀tọ̀, ó pé é ní nilo-Saharan..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ rẹ̀ sì fi ara pẹ́ ti Westerman tààrà ní abẹ́ ìsọ̀rí yìí..
wikipedia
yo
(f)Adamawa kún àkójọpọ̀ èdè yìí(g)ní ọdún 1963, Kordonian kúrò ní èdè kòtò-ń-kan ó di ọgbà kan náà pẹ̀lú Niger-Congo..
wikipedia
yo
Orúkọ wa yí padà, ó di Niger-Kordo (tàbí Congo-dòtaán)..
wikipedia
yo
Greenberg fura sí ìpè èdè àwọn èdè wọ̀nyí, ó sì tọ́ka síi wí pé /p/
wikipedia
yo
Èyí sì máa ń jẹyọ dáadáa nínú àwọn àfòmọ́ ìbẹ̀rẹ̀ àti àwọn ọ̀rọ̀ kòsémánìí kan nínú àwọn èdè yìí..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn Greenberg ní MuKaromaakati ṣe àtúpalẹ̀ àti àtúnpín àwọn èdè yìí, ó yọ̀ Kordonian, Mọ́mì, Wolof-R-Rful, Ijoid ati adáwa kuro nibẹ; àwọn ìyókù ni ó si pè ní ‘Western Nigritíọ́rì
wikipedia
yo
Ayé sì tẹ́wọ́ gba iṣẹ́ yìí gan-an ni láàrin àwọn olùwádìí ìjìnlẹ̀..
wikipedia
yo
Atunṣe gboogi waye lati owo Bennett ati Sterk (1977), won fi oju LÁMÈYÍ wo awon oro orukọ ti o fara jo ara wọn ninu awon ede wonyi..
wikipedia
yo
ìgbàgbọ wọn ni wí pé Kordoni àti Mọ́mì ti yà kúrò lára wọn..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí ni ìwọ̀ oòrùn Àtìláńtíìkì yà kúrò lára ìsọ̀rí èdè yìí tí a sì fún àwọn tí ó kú ní orúkọ àárín gbùngbùn Niger-Congo..
wikipedia
yo
Ara àwọn wọ̀nyí ni ila-oorun Adamawa, Gur, Kru ati ijó wa..
wikipedia
yo
Okan gboogi ise lori iwadii yii ni the Niger-cong languages (ben (Ben - Samuel 1989) je..
wikipedia
yo
ÀGBÉKALẸ̀ ÌSỌ̀RÍ ÈDÈ Niger-Congo gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ lónìí ni a ṣe àtẹ rẹ sí ìsàlẹ̀ yìí (Boyd 1989) nípa lílo àlàyé fún ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn..
wikipedia
yo
Nínú àtẹ yìí a rí, ‘Pro-Niger-Congo’ nínú èyí tó jẹ́ wí pé ‘Kortaọ̀mù’ ní ìsọ̀rí àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ yapa..
wikipedia
yo
Mọ́mì àti ìwọ̀ Oòrùn Atlantic ní ìsọ̀rí kejì tí ó tún yapa bẹ́ẹ̀, èyí tí wọ́n fi hàn wà lábẹ̀ ‘pro-kínní-Atlantic-Congooṣù
wikipedia
yo
Àwọn èyí tí ó tún dàbí rẹ̀ ni àwọn tí wọ́n pín sí abẹ́ ìsọ̀rí àárín gbùngbùn Niger-Congo..
wikipedia
yo
Láti ará ‘Pro-ìjọ-Congo’ ni ‘ijo’ ti yapa, lábẹ́ rẹ ni a ti rí ìjọ àti Decasal..
wikipedia
yo
Lábẹ́ ‘pro-ìjọ-Congo’, a rí ‘pro-do-gon-Congo’ èyí tí Dogon yapa láti ara rẹ..
wikipedia
yo
Lábẹ́ ‘Pro-dogon-Congo', a rí ‘pro-Volta-Congo’ tí ó pín sí ìwọ̀ oòrùn Vọta-Congo àti ìlà oòrùn Volta Congo (proto-Benue-kwa)..
wikipedia
yo
Ni a pa ìwọ̀ oòrùn Volta-Congo ni a ti wá rí Kru, Pre, Diyafo; aarin gbùngbùn Gur ati àdáwàwa (Bibi, Day, Kam àti U’’)..
wikipedia
yo
A le pe e ni Gur-Adamawa.ni apa ila oorun, ni a ti ri aarin gbùngbùn orile ede Nijiria ti ohun naa tun yapa, a si ri Banìṣàkósoòrùn Cross labẹ ila oorun yii..
wikipedia
yo
Lára Banrks Cross yìí ni Cross River ti yapa, nígbà tí a wá rí Banakókó lábẹ́ Banakókó Cross..
wikipedia
yo
Kordo ní agbègbè orí òkè nùbá ní orílẹ̀ èdè Sudan ni àwọn ènìyàn tí ó ń sọ èdè yìí wọ́pọ̀ sí jùlọ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ogun àti ọ̀tẹ̀ ti fọ́n ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn yìí ká..
wikipedia
yo
Àtẹ ìsàlẹ̀ yìí ni ó ṣe àkójọpọ̀ àwọn ìsọ̀rí èdè tí ó wà ní abẹ́ orí èdè kòdòfànían..
wikipedia
yo
Heníhìn pin sí ìlà oòrùn (ko, ìwọ̀nyíang); àárín gbùngbùn (KoAlib, lógol, bára, Eangang, utóró Láàrin ‘Central àti West' A rí tálákàmba; ni ìwọ̀ oòrùn (tiro àti Moro)..
wikipedia
yo
Mọ́mì ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà ni àwọn ènìyàn tí ó n sọ èdè yìí sọdọ sí Jùlọ..
wikipedia
yo
Awon Ihu ti a si ti ri awon ti ede won Pékà lati ara ori ede yii ni Mali, Côte d’Ivoire, Sierra Leone, Liberia, Burkina Faso, Senegal, Gábíàbíà, Guinea Bissan, Makódà, Banin, Ghana, Togo ati Nigeria (gbọ́kànyer 1989; Kasten 1991/ 1991/ó tó ènìyàn bíi Milionu mẹ́wàá sí méjìlá tí wọ́n n sọ o..
wikipedia
yo
nínú àtẹ yìiu a rí 'Proto-Mọ́mìʹ tí ó pín sí ìwọ̀ oòrùn àti ìlà oòrùn ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀..
wikipedia
yo
A wá rí ìwọ̀ oòrùn fúnrarẹ̀ tí ó tún wá pín sí àárín gbùngbùn tàbí gúúsù-ìwọ̀ oòrùn àti àríwá ìwọ̀ oòrùn..
wikipedia
yo
O fọ́nká lati enu odo Senegal titi dé orile ede Liberia..
wikipedia
yo
Ní àríwá ni a ti rí Fulfulde àti Wolof, Or, Cangin, Diọ̀la àti Pupel, Balanta, Conpdiah àti Konyagi, Bíáfàdá/pa/PA, Kobi/ka/ àti Banyin, Nakoko, Bioba Bi-K-Atlantic), súà, Tenene, SherBro àti Gola, Lmba..
wikipedia
yo
Ijoid apa guusu ile Nigeria ni a ti ri awon ti won n sọ ede yii..
wikipedia
yo
Jenewari ati Williamson (1989) ni won se agbekale ate isale yii fig 2.5..
wikipedia
yo
Nínú àtẹ yìí, a rí ‘Pro-ijo-id’ tí ó pín sí Deoras àti ijó..
wikipedia
yo
Dogon ènìyàn bíi idaji milionu miliọnu tí a bá pàdé ní ilẹ̀ Mali àti Bùrkínà Fasọ̀ ni wọ́n ń sọ èdè yìí..
wikipedia
yo
BenDor-Samuel àti àwọn ìyókù (1989) ni ó gbé àtẹ yìí kalẹ̀..
wikipedia
yo
Fig 2.6.Inú àtẹ yìí, a rì 'Proto dogon' tí o pin sí ìsọ̀rí mẹ́fà..
wikipedia
yo
Àwọn ìsò náà ní yìí (a) − Jamsay tegu, tòrò sojú, tene ka, tọmọ ka (b) [ −toro Soona, Tombaco Sooy, Kamo soo (D-D dom, ní ẹjẹ do (e) West-me-me me me (e) plate-an rere..
wikipedia
yo
DoGul dom (f)ìsọ̀rí kẹfà ni yànda dom, òoru yílle àti Naya tẹ̀gu..
wikipedia
yo
Àríwá Volta-Congo,Kru, Gur ati adáwa-uolúwa ní àwọn ẹ̀ka èdè tí a lè rí ní abẹ́ ìsọ̀rí ‘Àríwá Volta-Congo’ bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé àwọn èdè yìí ti fọ́nká orílẹ̀ Kruorílẹ̀-èdè Côte d’Ivoire àti Liberia ni a ti lè rí àwọn ènìyàn tí wọ́n ń sọ èdè yìí..
wikipedia
yo
Ó tó eniyan bíi mílíọ̀nù kan sí meji tí wọn ń sọ èdè yìí..
wikipedia
yo
Tí a bá wo àtẹ ìsàlẹ̀ yìí, a ó ṣe alabapade àwọn èdè bíi Dálíbù, tìẹgba, Seme àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ lára orí èdè 'okìbéèrè
wikipedia
yo
Nínú àtẹ yìí a rí ‘pro-Kru’ tí ó pín sí ìsọ̀rí mẹ́ta..
wikipedia
yo
Àwọn ìsọ̀rí náà níwọ̀n yìí (a)ila-oorun - Godie àti Kouya, DÍDÁ, Kwadia, Bkwe àti wane..
wikipedia
yo
(b)Iwọ-oorun -gago Complex, guere Complex, Bssa, Kláọ (d)ìsòrí kẹta ní àwọn bíi Ẹ́línìí, tiegba, Abrákò, Seme..
wikipedia
yo
Gurẹ̀ yìí gbajú gbajà dáadáa àti wí pé ọ̀pọ̀ ènìyàn ni ó ń sọ èdè yìí ní orílẹ̀ ayé..
wikipedia
yo
A lè rí àwọn ènìyàn tí wọ́n ń sọ èdè náà ní orílẹ̀ èdè bíi Côte d'Ivoire Ghana, Togo, Benin, Burkina Faso àti Nigeria..
wikipedia
yo
Ó tó èèyàn bíi mílíọ̀nù márùn-ún àti àbábọ̀ tí wọ́n ń sọ èdè yìí gẹ́gẹ́ bí manessy 91978) ti ṣe ìwádìí rẹ̀.Fi 2.8..8..
wikipedia
yo
Adamawa-uTekoa Ede ti o gbooro ni ede Adamawa-uolúwa..
wikipedia
yo
Ipẹ́ka rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ láti apá gù-iwo oòrùn Nàìjíríà títí dé Ariwa-iwo oorun Sudan..
wikipedia
yo
Apapo iye awon ti o n so ede Adamawa to Milionu kan ati aabo-Crozier ati Blench (1992); Grimes (1996)..
wikipedia
yo
Milionu meji le lẹ́gbẹ̀rún lọ́nà ọ̀ọ́dúnrún ní Barrétèau àti Monino (1978) tọ́ka sí gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń sọ èdè Ufiyè..
wikipedia
yo
Èyí túmọ̀ sí pé àpapọ̀ àwọn tí ó ń sọ èdè adáwà-uolúwanímù ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ jẹ́ mílíọ̀nù mẹ́rìndín ní ẹgbàá lọ́nà ọgọ́rùn-ún láì ka àwọn tí ó ń sọ èdè Ṣàngó mọ́ ọ.Fi 2.9..
wikipedia
yo
Nínú àtẹ yìí a rí 'Proto-adáwà-uolúwa' tí ó pín sí ọ̀nà méjì ní ìbẹ̀rẹ̀ àpẹẹrẹ..
wikipedia
yo
Uteli - gbàyà; Banda, NCgbandi, ṣeré, ngbaka àti ḿbá; Zande..
wikipedia
yo
South Volta-CongoBennett ati Sterk (1977) pe 'South Volta-Congo ní àárín gbùngbùn ariwi Niger-Congo..
wikipedia
yo
Ayaa waye nipa yíyapa ti o wa ye laarin Kwa àti Benue Congo nítorí pe won sun mó ara won pẹkípẹkí-Greenberg (1963)..
wikipedia
yo
Bíi mílíọ̀nù lọ́nà ogún ní Grimes (1996) fi yé wa wí pe ó ń sọ èdè náà..
wikipedia
yo
Greenbery (1963a) pín-in sí ìsọ̀rí mẹjọ, ó sì so àwọn èdè ààrin gbùngbùn Togo pọ̀ mọ́ ìsọ̀rí tirẹ̀..
wikipedia
yo
Fig 2.10.Nínú àtẹ yìí a rí 'proto-kwa' tí ó pín sí ìsọ̀rí mẹ́fà ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀..
wikipedia
yo
lábẹ́ pọ̀uu ni a ti rí erierie àti Mbatto tano - eléyìí pín sí ìsọ̀rí mẹ́rin..
wikipedia
yo
(ẹ)guan - o tun pin si guusu nibi ti a ti ri kodara -Àgbàsan ati Larten-ín-peori..
wikipedia
yo
Ka-Togo ;- ìsọ̀rí eléyìí pin sí AAvme, Vgbo-ta-fi; Kpò, Ahlo, Bowìrì (K-Togo); Râ, Animere..
wikipedia
yo
Àwọn orílẹ̀ èdè púpọ̀ ni ó ní àwọn èèyàn tí wọ́n ń sọ èdè yìí, ó sì sọ́dọ̀ sí apá gúúsù ilẹ̀ Nigeria dáadáa..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni ìlú bíi Cameroon, Congo, Car, DRC, tondojú, Uganda, Kẹ́ńyà, Mozambique, Angola, Rwanda, Burundi, Namibia, Zambia, Malawi, Zimbabwe, Gàbọ̀n, Lesotho, Ṣamalia àti àwọn èdè yìí kalẹ́..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí Grimes (1996) ṣe wádìí rẹ̀, èdè Yorùbá àti Igbo ni ó tóbi jùlọ nínú ẹ̀ka èdè tí a pè ní Benue-Congo, ìsọ̀rí ìwọ̀ oòrùn Benue-Congo ni o si pin àwọn èdè wọ̀nyí sí..
wikipedia
yo
Fig 2.11.Nínú àtẹ yìí a rí 'Proto-Benue-Congo' tí ò pín sí ìsọ̀rí méjì pàtàkì..
wikipedia
yo
Nígbà tí a sì rí Cross River ní abẹ́ Bantinútinú-Cross..
wikipedia
yo
Ní ìparí, ó fihàn gbangba wí pé èdè Niger-Congo tóbi tààrà àti wí pé orílẹ̀ èdè Áfíríkà ni o pẹ̀ka sí ọ̀pọ̀ nínú àwọn èdè yìí ni ó gbálẹ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ ṣùgbọ́n a rí lára wọn ti ìgbà ti fẹ́rẹ̀ tan lórí wọn..
wikipedia
yo
Àwọn wọ̀nyí ni èdè mìíràn ti fẹ́ máa gba ṣáá mọ́ lọ́wọ́ àwọn ìdí bíi, òṣèlú, ogun, ọ̀làjú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ni ó sì ṣe okùnfà èyí..
wikipedia
yo
Ní pataki jùlọ, gbogbo èdè yìí náà kọ́ ni àwọn lámèyítọ́ èdè fi ohùn ṣe ọ̀kan lé lórí lábẹ́ ìsọ̀rí tí wọ́n wà ṣugbọn ọpọlọpọ ni ‘Ẹ̀bi’ rẹ̀ fi ojú hàn gbangba..
wikipedia
yo
Ní ìparí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀mọ̀wé ni wọ́n ti ṣe iṣẹ́ ìwádìí lórí rẹ̀ ṣùgbọ́n ààyè sì tún ṣí sílẹ̀ fún àwọn ìpẹ́ẹ̀rẹ̀ tulẹ̀ láti ṣe iṣẹ́ ìwádìí àti lámèyítọ́ lórí ẹ̀ka èdè Niger-Congo.Ìtọ́kasí àwọn èdèàwọn èdè Áfríkà..
wikipedia
yo
Kordoníà àánùni agbègbè ori òkè Nuba ní orílẹ̀ èdè Sudan ni àwọn ènìyàn tí ó ń sọ èdè yìí wọ́pọ̀ sí júlọ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ogun àti ọ̀tẹ̀ ti fọ́n ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn yìí ká..
wikipedia
yo
Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà ni àwọn ènìyàn tí ó ń sọ èdè yìí sọ́dọ̀ sí Jùlọ..
wikipedia
yo
Awon Ihu ti a si ti ri awon ti ede won Pékà lati ara ori ede yii ni Mali, Côte d’Ivoire, Sierra Leone, Liberia, Burkina Faso, Senegal, Gábíà, Guinea Bissau, Mauritania, Banin, Ghana, Togo ati Nigeria (gbọ́kànyer 1989; Kasten 1991z 1991/2).Ó tó ènìyàn bíi Milionu mẹ́wàá sí méjìlá tí wọ́n ń sọ́ o..
wikipedia
yo
ÀtìláńtíìkìỌ́káGẸ́GẸ́ BÍ ORÚKỌ RẸ TI FI ARA HÀN ìwọ̀ oòrùn ÁFÍRÍKÀ, NÍ Ẹ̀bà ÒKUN Àtìláńtíìkì ní èdè yìí SỌ́DỌ̀ sí jùlọ..
wikipedia
yo
Ní àríwá ni a ti rí Fulfulde àti Wolof, Or, Cangin, Diọ̀la àti Pupel, Balanta, Conp/Be àti Konyagi, biata/PAjade, Kobiana/K/ga àti Banyin, Nalú, Bioba Bi-Atlantic), Ṣúà, Tenene, SherBro àti Gola, Limàwọn as Afrika.. Afrika..
wikipedia
yo
APÁ GÚÚSÙ ILẸ̀ NIGERIA NI A TI RÍ ÀWỌN TÍ WỌ́N Ń SỌ ÈDÈ YÌÍ..
wikipedia
yo
Jenewari ati Williamson (1989) ni wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ àtẹ ìsàlẹ̀ yìí nínú àtẹ yìí, a rí ‘Pro-ijo-id’ tí ó pín sí Deyọ̀ọ̀da àti ijó..
wikipedia
yo
Inú àtẹ yìí, a rí ‘Pro dogon' tí o pin sí ìsọ̀rí mẹfa..
wikipedia
yo
Àwọn ìsò náà ní yìí (A) - Jamsay tegugu, tọrọ pà, tene ka, tọmọ ka (b) Nroko toro soo, Tombaco Toṣọ̀ọ́, Kamo O (D- Yól dom, ẹjẹ do (e) West-e-me Y me (e plate-an rere.. dom..
wikipedia
yo
DoGul dom (f)Ìṣọ̀rí Kẹfà ni yánda dom, orù yílle àti Naya Tegu.Iye àwọn tí ó ń sọ èdè yìí jẹ́ 100,000..
wikipedia
yo
(Ọ̀kẹ́marun-un) orile ede ti won ti n so ede yii ni Mali, ati Burkina Fasoitọkasi Afrika..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Côte d’Ivoire àti Liberia ni a ti lè rí àwọn ènìyàn tí wọ́n ń sọ èdè yìí..
wikipedia
yo
Tí a bá wo àtẹ ìsàlẹ̀ yìí, a ó ṣe alabapade àwọn èdè bíi Dálíbù, tìẹgba, Seme àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ lára orí èdè 'okjárí
wikipedia
yo
nínú àtẹ yìí a rí 'Proto-Kru' tí ó pín sí ìsọ̀rí mẹ́ta..
wikipedia
yo
(b)Iwọ-oorun -gago Complex, gueré Complex, Bssa, Kláọ (d)ìsòrí kẹta ní àwọn bíi Ẹ́línìí, Tígun, Abrákò, Seme...
wikipedia
yo
Ipẹ́ rẹ bẹ̀rẹ̀ láti apá gugù-iwo oòrùn Nàìjíríà títí dé Ariwa-iwo oorun Sudan..
wikipedia
yo
Èyí túmọ̀ sí pé àpapọ̀ àwọn tí ó ń sọ èdè adáwà-uolúwanímù ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ jẹ́ mílíọ̀nù mẹ́rìndín ní ẹgbàá lọ́nà ọgọ́rùn-ún láì ka àwọn tí ó ń sọ èdè Ṣàngó mọ́ ọ.Nínú àtẹ yìí a rí 'Pro-adá-wà-u=’’ tí ó pín sí ọ̀nà méjì ní ìbẹ̀rẹ̀ àpẹẹrẹ..
wikipedia
yo
Uteli - gbàyà; Banda, NCgbandi, ṣeré, ngbaka àti ḿbá; Zande...
wikipedia
yo
Nínú àtẹ yìí a rí ‘pro-Benue-Congo’ tí ó pín sí ìsọ̀rí méjì pàtàkì..
wikipedia
yo