cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àwọn oríṣìíríṣìí kílíìkì wọnyi ló mú kí èdè KristiIṣan yàtọ̀..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ ninu èdè Nama, ogun ní kílíìkì tí wọ́n ń lọ nígbà tí wọ́n ń lo mẹtalelọgọrin ninu èdè KXby tí ó jẹ́ ọ̀kan lára èdè KhoIṣan..
wikipedia
yo
Ní àfikún, àádọ́rùn-ún onírurú kọ́ńsónáǹtì kílíìkì ni wọ́n ń lọ ní Gwí tí ohun náà jẹ́ ọ̀kan lára èdè Khosian wọ̀nyí..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ kílíìkì námàgbogbo àwọn kọ́ńsónáǹtì kílíìkì àti èyí tí kìí ṣe kílíìkì ló máa ń fara hàn ní ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ tí fáwẹ́lì sì máa ń tẹ̀lé e..
wikipedia
yo
Ìwọ̀nba kọ́ńsónáǹtì Bí àpẹẹrẹ /b// /// /n/ /r/ àti /l/ ló lè jẹ yọ láàrin fáwẹ́lì, díẹ̀ sì lè farahàn ní ẹ̀yìn ọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Ìró ohùnàwọn èdè Khosàn máa ń ṣàfihàn oríṣìíríṣìí ìró ohùn, bí àpẹẹrẹ, òwòòkè'an ní ipele ohun ààrùn oríṣìí mẹ́run, ó sì ní ìpele ohùn òkè kan.gírámà ọ̀rọ̀ àti ìhun gbólóhùn àwọn èdè Khoiṣan yàtọ̀ síra láàrín ara wọn..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ orúkọ ìsọ̀rí mẹ́ta ni ọ̀rọ̀ Adárúkọ KhoIṣan pin sí; bí a bá wòó, nípasẹ̀ ńdánda, akọ, abo àti àjọní ni ó pín sí..
wikipedia
yo
Ninu Kxo, fun apẹẹrẹ, Jenda ninu oro-orukọ aláìlẹ́mìí tun maa n ni nǹkan se pelu irisi, bi apẹẹrẹ, ako ni i se pelu gigun, ti tọ si tobi, nigba ti abo ni i se pelu NKenken kukuru, Gbígbòòrò ti ko si tobi oríṣìíríṣìí mọ́fíìmù ni won fi n pari ọkọọkan awon jenda wọnyi..
wikipedia
yo
KhoIṣan ,English, Yorùbá ,Khoe-B,man ,ọkùnrin ,Khoe-s,woman, obìnrin ,oríṣìíríṣìí nọmba mẹta ni wọ́n ní, àwọn ní ẹyọ, onimeji ati ọpọ..
wikipedia
yo
Nobapẹẹrẹ láti inú èdè nàró Marù (akọ), Female (Abo), Common (Akọ/Abo) , ,sa Dual ,Sara ,Sara, Khoara pl Lẹ̀gbàdades Dzi Naoro-iṣẹ àbùdá girama tí ó sáá máa ń jẹ yọ nínú àwọn èdè KhoIsan ní lilo ọ̀rọ̀-iṣẹ́ àkànkonuko (verb Comlo) nígbà tí èdè Gẹ̀ẹ́sì ń lo ọ̀rọ̀ atọ́kùn tàbí ọ̀rọ̀-iṣẹ́ kan (single verb) apẹẹrẹ English, ìtọ́jú, enter go + enter..
wikipedia
yo
Àsìkò (Tense) Erunmi ni a máa ń lò láti fi àsìkò hàn nínú èdè Khoekhoe àti nípa lílo afọ̀rọ̀ ẹ̀yin nínú èdè Kxo, buga àti //ani nínú àwọn èdè Kalahari East Kxo, àfòmọ́ ẹ̀yin ló ń fi ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ti kọjá han (past Tense), ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ tí ó lòdì àti Jérondi han nígbà tí ìṣẹ̀lẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ àti tí ọjọ́ iwájú ń lọ ẹ̀run..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà lọ́mọ sórí ninu èdè nàró, g//ana, G/UI ati ++haba..
wikipedia
yo
Ibà ìṣẹ̀lẹ̀ mana nìkan ni ó ń lo ìba ìṣẹ̀lẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ìṣẹ̀dá (Morphological Category) ó sì ya ìba ìṣẹ̀lẹ̀ Àṣẹ́tán sọ́tọ̀ sí àìṣẹ̀tàn ìyísódì ẹ̀run tàbí àfòmọ́ ẹ̀yin ni wọ́n ń lò fún ìyísódì (ekhoe Tam; g//ana G/UI àti ++haba tamatema) ń lo ẹ̀rún fún ìyísódì nígbà tí (Kpátákòe //am..
wikipedia
yo
Buya-be) n lo àfòmọ́ ẹ̀yin, nígbà mìíràn wọ́n ń lọ mejeeji..
wikipedia
yo
Ètò ọ̀rọ̀ètò ọ̀rọ̀ ti àwọn èdè KhoIṣan tí à ń sọ wọnyi máa ń lò ní (Svo-subject-verb-object) OLUWA ọ̀rọ̀-ìṣe ati abo tabi (Aṣọe-ṣu-object-verb)..
wikipedia
yo
ọ̀rọ̀ èdè (Votamueller) àfihàn ìgbésí ayé àwọn olùṣọ́ èdè KhoIsan ni ọ̀rọ̀-èdè (Vor€$)) wọ́n jẹ́..
wikipedia
yo
Ní ìwọ̀n ìgbà tí àwọn olùṣọ́ èdè wọ̀nyí ń gbé pọ̀ pẹ̀lú àwọn ìṣẹ̀dá míìra, èyí mú kí wọ́n ní àwọn ọ̀rọ̀-èdè tí ó súnmọ́ òde ṣíṣe, ẹranko, koríko àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ ọ̀pọ̀ àwọn èdè wọ̀nyí ni kò ní àkọsílẹ̀ ṣùgbọ́n námà àti nàró ní àkọsílẹ̀ àti ohun èlò ìkọ́ni..
wikipedia
yo
námà ní pàtàkì ti wà ní àkọsílẹ̀ láti ọjọ́ pípẹ́...
wikipedia
yo
Ìlọrin ni olú-ìlú ìpínlẹ̀ Kwara ní ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Gẹgẹ bi àbáyọrí ìkà èniyàn ọdún 2006 ní Nàìjíríà, ìlú Ìlọrin ní Olugbe 777,667, eyi mú kí ó jẹ́ ìlú keje tí ó ní Olugbe jùlọ ní Nàìjíríà.Awon Ìtọ́kasí oluilu ipinle Naijiria..
wikipedia
yo
Ṣebíimier nowàkì (lati ọdun 1897 titi di osu wara ojo ketala odun 1937 je omo ỉu POUlánNA ti oje arin- oniede oni?. ati Aya woran ti a bi ni ilu Stiryi..
wikipedia
yo
Lẹhin Ogun Agbaye Alakoko ọgbẹ ni Ilu Poznani lati ọdun 1931 titi di ọdun 1936 orin, Ogun kẹkẹ jákè jádò Ilu alawọ dudu..
wikipedia
yo
Orin Irinajo ti Oro egberun lona ogoji kilomita (40.000 km)..
wikipedia
yo
Tog ni eni akoko ti òkókó seiru nkan bayi.O ti kọ iṣe yi si inu iwe ti a pe oruko re ni Rowerem i PieZ Pzez Czarny lad (kẹkẹ ati ese jákè jado ile alawo dudu).
wikipedia
yo
le ri àpèjọro eji ninu èrò aketaneti ilu pólánNATAEN..
wikipedia
yo
Lítíréṣọ̀ tàbí iṣẹ́ọ̀nàTàbíohun tí lítíréṣọ̀ jẹ́eléyìí náà kò ṣàì ní orírun tirẹ̀ láti inú èdè Latin "litere" Èyí ni àwọn Gẹ̀ẹ́sì ya wọ inú èdè wọn tí wọ́n ń pè ní léte rature"ìtumọ̀ tí a fún lítíréṣọ̀ máa ń yípadà láti ọ̀dọ̀ ẹ̀yà ènìyàn kan sí èkejì láti ìgbà dé ìgbà..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní Nigeria ni wọ́n bùdó sí jùlọ.Ìtàntí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa ojúlówó àwọn ọmọ Yorùbá ní ilẹ̀ Yorùbá òde-òní Ìjẹ̀ṣà jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ojúlówó ọmọ Yorùbá tí kò ṣe fi ọwọ́ rọ́ sẹ́yìn nínú ìtàn àwọn Yorùbá..
wikipedia
yo
OríIṣié ìtàn ni a sí gbọ́ nípa orírun Ìjẹ̀ṣà gẹ́gẹ́ bí ojúlówó Yorùbá kò dá a ti le gbọ́ wí pé olórí àwọn Ìjẹ̀ṣà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ méjejẹ ti Odùduwà bí.Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtàn ni a gbọ́ nípa ìṣẹ̀dálẹ̀ Ìjẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
Ó sì dàbí ẹni pé ó sọ̀rọ̀ díẹ̀ láti sọ pé ọ̀kan ní fìdí múlẹ̀ jùlọ.Lára ìtàn tí a gbọ́ ni wí pé ó jẹ́ àṣà fún àwọn ènìyàn jàkànjàkàn láti wá bá Ajíbógun ni ibùdó rẹ̀, àwọn ènìyàn wọ̀nyí ni à ń pè ní “Ìjọ tí a sá”
wikipedia
yo
Ní ìtẹ̀síwájú, ìtàn sọ fún wa wí pé Ọ̀gùngírì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó bá Ajíbógun kúrò ní Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Bakanna ni itan so pe ojid lo jẹ Ogboni si ilu ti Ijebu-Jẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
A sì tún gbọ́ wí pé nígbà tí Ajíbógun kúrò ni Ilé-Ifẹ̀, Ilé-Ido ni ó kọ́kọ́ dúró sí láti ilé Ido yí ló ti lọ sin òkú Olófìn (Odùduwà) ní Ilé-Ifẹ̀, lẹ́yìn èyí ni a gbọ́ wí pé igbádáyé ni Ajíbógun padà sí, tí ó sì kú síbẹ̀..
wikipedia
yo
Ọkà-ó-kílé tí ó jẹ́ dáódù fún Ajíbógun ni ó jẹ́ ọwá sí ìlú- Ìlọ́wá tí òun náà sì sun ibẹ̀, bákannã ni Ọ̀bàràbara tí a mọ̀ sí Olókun..
wikipedia
yo
Óyaa ni eniti ó jé Ọwá àkọ́kọ́ sí ìlú Iléṣà tí ó ní.Bátọ ni a tún rí ìtàn míràn tó sọ fún wa nípa ọwá Obokun ti ilẹ̀-Ìjẹ̀ṣà wí pé nígbà tí Odùduwà tó n se bàbà fún (Ajibogun) dàgbà tí ojú rẹ̀ fọ́ ní ifá mẹ́tadínrègún ni kí wọ́n lọ bu omi òkun wá kí ojú Odùduwà bàbá wọn lè là..
wikipedia
yo
Báyìí ni ó wà pé àwọn ọmọ rẹ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan èjèèjì wí pé kí wọn lọ bu omi lókun wá fún ìtọ́jú ojú ọ̀hún, ṣùgbọ́n èyí Ọwá rẹ̀ ló gbà láti lọ bu omi okun náà wá..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ń lo baba rẹ̀ fún ní idà tí a mọ̀ sí ìdá ìṣègùn pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ agbára, a gbọ́ wí pé nígbà tí ó ń lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣòro àti ìdàmú ló bá pàdé ní ojú ọ̀nà rẹ̀ ṣùgbọ́n ó ṣẹ́gun wọn pẹ̀lú ìdá ìṣègùn ọwọ́ rẹ̀, ṣùgbọ́n kí ó tó dé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ló ti sọ ìrètí nu èrò yìí ló mú kí bàbá rẹ̀ gan-an pàápàá sọ ìrètí nù, èrò yìí ló mú kí bàbá pín gbogbo ogún àti àwọn ohun ìní rẹ̀ fún àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ (Ọwá)ṣùgbọ́n ìyàlẹ́nu ló jẹ́ fún àwọn ènìyàn àti bàbá wí pé ó lè padà dé mọ́..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó dé wọ́n fi omi òkun fọ́ ojú baba wọn ó sì là padà, lẹ́yìn èyí ló wà bí bàbá lérè wí pé àwọn ẹ̀gbọ́n òun ń kó bàbá sì ṣàlàyé fún pé ó ń rò pé kò lè padà wá sí ilẹ̀ mọ́ àti wí pé ó ń ti pín gbogbo ogún fún àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀..
wikipedia
yo
Ajíbogun bínú gidi, ó wá béèrè wí pé kí ni ogún tí òun báyìí, bàbá rẹ̀ ní kò sí nkan-kan mọ́ àfi ìdá ìṣègùn tí ó wà ní ọwọ́ rẹ̀ nìkan ló kù, inú bí ajíbogun ó fa idà yọ láti fi gé bàbá rẹ̀, ṣùgbọ́n idà bá adé ó sì gé jọ̀wọ́ iwájú adé náà, lẹ́yìn èyí ni bàbá rẹ̀ gbé adé náà fún, nítorí pé ó ṣe Akin àti akíkanjú ènìyàn, ṣùgbọ́n bàbá rẹ̀ sọ fún wí pé láti òní lọ kò gbọdọ̀ dé adé tí ó ní jọ̀wọ́jọw létí mọ́, àti ìgbàyí ló ti di èwọ̀ fún gbogbo Ọwá tí ó bá jẹ ní Iléṣà.Ìtàn míràn ni pé, lẹ́yìn ìgbàtí Ajíbógun ti parí iṣẹ́ tí bàbá rán tán ni ó kúrò ní Ilé-Ifẹ̀ láti lọ ṣe ìbẹ̀wò sí ìlú àwọn bàbá rẹ̀..
wikipedia
yo
Lára àwọn ìlú ti Ajíbógun gbà kò jà ni oṣù àti àwọn ilú míràn, a gbọ́ wí pé, Ọkà-ó-kílẹ̀ tí ó jẹ́ dáódù fúnbogun ni ó jẹ́ Ọwári sí ìlú Apólé tí wọ́n ń sí ń pè ní Ọwári..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ fún wa wí pé ipòle yìí ni ọkà-ófi jẹ́ Ọwá ti rẹ̀ sí ṣùgbọ́n òun àti àwọn ará ìlú kò gbọ́ ara wọn yé rárá nítorí agbára tí ó ní, ṣùgbọ́n ó ṣẹlẹ̀ wí pé ọ̀tẹ̀ yìí bẹ̀rẹ̀sí ní pọ̀ sí láàrin àwọn ará ìlú pẹ̀lú ọba, ọ̀tẹ̀ yìí ló fa ìjà tí ó pín ìlú sí méjì..
wikipedia
yo
Lára àwọn ti ó kó ara jọ ni wọ́n sọ gbólóhùn kan pé “In jẹ́ àṣà” tí ó túmọ̀ sí pé “ ẹ̀jẹ̀ ka ṣá ” èyí ni wọ́n yípadà sí Ìjẹ̀ṣà, àwọn wọ̀nyí ni wọ́n ló tẹ ìlú Iléṣà gan-gan dó..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí wọ́n tẹ ìlú Iléṣà dó ní àwọn olóyè tí wọ́n kúrò ní ìlú ipòlé pe ara wọn jọ pé ó yẹ kí àwọn ní ọba, wọ́n wá pa ìmọ̀ pọ̀ pé kí wọ́n lọ mú Ọwáluṣẹ́ tí ṣe àbúrò ọkà-ó-kílé kí ó jẹ ọba wọn, wọ́n ṣe bẹ̃ lóòtọ́ Ọwáluṣẹ́ sì jẹ́ ọba àkọ́kọ́ ní ìlú Iléṣà..
wikipedia
yo
Ìgbátí ti ọkà-ó-kílẹ̀ gbọ́ ni ipò ó ránṣẹ́ sí Ọwáluṣẹ́ pé kí ó wá..
wikipedia
yo
Óyaa sí ṣe bẹ gẹ́gẹ́, ìgbàtí ó dé ọdọ ọká-ónu náà ìdá sí etí Ọwáluṣẹ́, etí kan sí jábọ̀, ìgbàtí Ọwáluṣẹ́ padà sí Iléṣà òun a ti Ọwá (ọkà-o-kílẹ̀) kò rí ara wọn, àti ẹrẹ̀yí ni ọkà- òkú ti gẹ̀gùn pé gbogbo ọdún tí wọ́n bá fẹ́ ṣe ni iléṣa wọn gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ ṣe ti ipò titi di àsìkò yìí..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn gbogbo rògbòdìyàn yìí ni ọkà-ó-kílẹ̀ (Ọwá) pinu láti bá gbogbo ara ipò ṣe ìpàdé pọ̀, ohun tí ó ṣe lé ní ìpàdé ni pé ọká-ó-kílẹ̀ ṣe àlàyé pé òun fẹ́ Bámidélé láàrin wọn (fẹ́ kú) ó fún wọn ní oṣù mẹ́ta, lẹ́yìn oṣù kan ará ìlú ló bá pé ṣe kò fẹ́ wọ ilé mọ́ ilẹ̀ mọ́ ni, ṣùgbọ́n ojú ti fẹ́ má tì Ọwári nítorí oró ọ̀hún ti di yéye láàárín ìgboro.Ìgbà tí ó di ọjọ́ tí ó fẹ́ wọ ilé ó jẹ́ ààrin òru bí Ọwári ṣe wọ ilé ní gbogbo ìgboro dàrú nítorí gbiri gbiri tí wọ́n gbọ́ wọ́n sáré kiri, kò pẹ́ ni àwọn kan rí tí wọ́n sì fi ariwo bo ẹnu pé Ọwá ti rí o, Ọwá ti rí o, èyí ni wọ́n yí padà tí ó di Ọwá..
wikipedia
yo
Ìdí sì ni yìí tí ówà kò gbọdọ̀ fi dé ibẹ̀ títí di àsìkò yìí.Ìlú mẹ́ta ló kúrò ní ipòlé, lára wọn ni ipòlé, ìjàkúrò àti ẹ̀fọn alààyè..
wikipedia
yo
Ìdí nì yí tí wọ́n ma ń sọ pé“Ọ̀pá ipò kù ogún ìjà kú ku ọgbọ́n ẹ̀fọn-alààyè wọn kú mẹ́ta gẹ́gẹ́”àti ìgbàyí ló ti di òrìṣà sí ìlú ipòlé àti agbègbè Ìjẹ̀ṣà.Àwọn ìlú ìjẹàti a bá sọ̀rọ̀ nípa àwọn tí ó wà ní abẹ́ Ìjẹ̀ṣà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìlú ni a lè rí tọ́kasí lábẹ́ wọn..
wikipedia
yo
Lára àwọn ìlú wọ̀nyí ni a ti rí ìlú ńláńlá àti kékeré.Àwọn ìlú náà ni wọ̀nyí(1)ipò )iro/3)kunkún(4)2)di(5)8(6)Odò(7]Olówu(8)ìpèrin(9(ii)kọ(10)Ìwà-rajà(11) (12)rìn(13)Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà(14)ìpètù-Jẹ̀ṣà(15)Erin-Ìjẹ̀ṣà(16) (17) (18–ibú19)ìkìwá (Ifẹ̀)wàrà) Òkè-22) (help)kunkún(24) (ilẹ̀ sí-ilẹ̀26) ìpẹ̀tù–ìpètù-28) (29)i (itagúnmọ́) gbára) Ọmọ)33)i (ilẹ̀ṣáàwọn oyè pàtàkì ní Ìjèṣà òye ló wà ní ilẹ̀ lòkàn ó jó kan..
wikipedia
yo
Pàápàá ní ìlú Iléṣà gangan, bẹ̀ pẹ̀lú ní àwọn oyè míràn tún wà ní ààrin àdúgbò..
wikipedia
yo
Bákan náà ni wọ́n ń jẹ àwọn oyè bí baálẹ̀, lọ́jà ní àwọn ìlú kékèké abẹ́ wọn..
wikipedia
yo
Lára àwọn oye pàtàkì tí ó wà ní ìlú Iléṣà gangan ni wọ̀nyí.(1)Lẹ́jọ́ )Ara Risa)we(4) lọ́rọ̀6(lọ̀rọ̀)Ól-L(7) Ni)sawé(9)Jimọ (10)sa àti àti11) ríseeto òṣèlú àti ètò ìjọba àwọn ìjẹàti a bá wo ètò òṣèlú tàbí ètò iṣẹ́ ìjọba ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà a ó rí wí pé ó jẹ́ ètò iṣẹ́ ìjọba tí ó dára..
wikipedia
yo
Nítorí pé, ọba lọ jẹ́ olórí fún gbogbo ìlú tí ó máa ń pa àṣẹ bákan náà ni wọ́n ní àwọn olórí àdúgbò kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú àwọn ìjòyè..
wikipedia
yo
Àwọn olórí yìí náà tún ní àwọn àsomọ́gbé kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú iṣẹ́ olúkálùkù..
wikipedia
yo
Ìyàlobinrin wà fún ọ̀rọ̀ àwọn obinrin ní àdúgbò, baba lórí ọmọ wa fún ọ̀rọ̀ àwọn ọ̀dọ́..
wikipedia
yo
Tí ọ̀rọ̀ kan bá ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ọ̀dọ́ tabi láàárín àgbà tí ó wà ní àdúgbò..
wikipedia
yo
Wọ́n á gbé ẹjọ́ náà lọ sí ilé baba lórí ọmọ tí baba lórí ọmọ bá parí ọ̀rọ̀ náà tí wọn a tari rẹ̀ sí olórí-àdúgbò àti àwọn ìjòyè rẹ̀ tí àwọn ìjòyè àti olórí àdúgbò náà kò bá rí ọ̀rọ̀ náà yanjú wọ́n á gbé ọ di ọ̀dọ̀ ọwá (ọba wọn) àti àwọn ìjòyè rẹ̀ fún ẹjọ́ dídá..
wikipedia
yo
Tí a bá wá rí ẹjọ́ tí Ọwá kò lè parí wọn a ní kí oníjà méjì náà lọ búra ní ẹ̀yìnkùlé Ọwá, níbíyí ènìyàn kò le ṣe èké kí ó lọ búra ní bẹ̀ nítorí kò sí ohun tí a sọ tí kò ní ṣẹlẹ̀.Àṣà àwọn ìjẹ́àtiàti a bá sọ̀rọ̀ nípa àṣà ní ilẹ̀ Yorùbá lónìí, a ó rí wí pé kò sí ojúlówó ọmọ Yorùbá tí kò ní àṣà, àmọ́ àṣà wa lè yàtọ̀ láti ibìkan sí ibòmíràn..
wikipedia
yo
Lára àwọn ojúlówó ọmọ Yorùbá tí ó ní àṣà ni a ti ri àwọn Ìjẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
Tí a bá sì n sọ̀rọ̀ nípa àṣà, àṣà jẹ́ ohun tí agbègbè kan ń ṣe yálà nínú ìwà wọn, ẹ̀sìn wọn, tàbí nínú ìṣesí wọn.Oúnjẹ jẹ́ ohun tí kò ṣe fi ọwọ́ rọ́ sẹ́yìn ní àwùjọ, bẹ̃ sì ní àwọn agbègbè kọ̀ọ̀kan ni àwọn oúnjẹ tí wọ́n fẹ́ràn..
wikipedia
yo
Ti a bá sọ̀rọ̀ nípa oúnjẹ ti Ìjẹ̀ṣà fẹ́ràn jù tàbí oúnjẹ tí ó jẹ́ oúnjẹ pàtàkì a ò ni ṣàì láì dárúkọ iyán, nítorí iyán ni oúnjẹ pàtàkì ti Ìjẹ̀ṣà máa ń jẹ, bí ó tilẹ̀jẹ́ pé wọ́n tún ní àwọn oúnjẹ míràn bí àmàlà, ẹ̀bà, fùfú, ẹ̀wà, ìrẹsì abbl..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n iyán ni ọba oúnjẹ wọn .Ìjẹ̀ṣà lè jẹ́ iyán ní Emeeta ní Ojúmọ́ tàbí ní gbogbo ìgbà àti àkókò nítorí náà, iyán jẹ oúnjẹ fún Ìjẹ̀ṣà.Ìjọ tí ijó jíjó kò sí àdúgbò tí kò ní ijó tàbí orin tí wọ́n, àwọn Òǹdó ń kọ obitun, Ìlàjẹ àti Ìkálẹ̀ n kó bírídò, bẹ̃ ní ti àwọn Ìjẹ̀ṣà pẹ̀lú Iléṣà ń kọ orin àdámọ̀, bẹ̃ni wọ́n tún jọ ijó ìkanga àti ijó lóyè pẹ̀lú ìlú bẹ̀ǹbẹ̀ àti orin Olùṣọ́ga bákannáà..
wikipedia
yo
onírurú orin ni a mọ Ìjẹ̀ṣà mọ ṣùgbọ́n ìkanga àti lóye ni ó jẹ́ orin ìpìlẹ̀ wọn tí wọ́n máa ń kọ.Ìyẹn máa tú jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ibi tí a ti lè rí àṣà àti èdè Yorùbá bákannáà ni gbogbo àwọn ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan tún ní àṣà ìwọṣọ ti wọn..
wikipedia
yo
Àwọn obìnrin Ìjẹ̀ṣà máa ńwọ aṣọ àfi tó jẹ́ ìró àti bùba bẹ̃ni àwọn ọkùnrin wọn máa ń wo èsìkí àti ṣòkòtò ẹlẹ́nu nlá pẹ̀lú fìlà àlàbankátà.Oge ṣíṣeèyí jẹ́ àṣà tí ó sábà máa ń súyọ láàárín àwọn obìnrin pàápàá jùlọ àwọn ọ̀dọ́..
wikipedia
yo
Àwọn obìnrin Ìjẹ̀ṣà máa ń lọ́ kòpa, tiro, osùn láti fi ṣoge.Àwọn akọni Ìjẹ̀ṣàgbègbèragbàdúrà ènìyàn ìlú Ijádeníbi Ìjèṣà jẹ́ alákíkanjú àti jagunjagun ènìyàn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun ni àwọn Ìjèṣà ní pa nínú rẹ̀, ní àkókò ogun káríayé ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Lára irú àwọn ogun bẹ́ẹ̀ tí àwọn Ìjẹ̀ṣà jà á ní ogun Ìbàdàn, ogun jàlúmù àti ogun KIRI tàbí ogun Èkìtì parapọ̀..
wikipedia
yo
Ogún Èkìtì parapọ̀ bèrè ni ọdún 1877, ó sì perí ni ọdún 1886..
wikipedia
yo
Eni tí ó jé bí aṣíwájú ògún pàtàkì yìí ni ọkùnrin alájagun Ìjẹ̀ṣà kan tí orúkọ rẹ̀ ń jé gbèrin .Ògún Ẹ̀kìtì parapọ̀ yìí ni ó mú orúkọ ògeden dúró ṣinṣin nínú ìtàn Yorùbá Oghon náà sí jà fún ọdún mẹsan gbáko ọdún 1910 ni ògèdèǹgbé kú.Ohun kan tí àwọn Ìjẹ̀ṣà ṣe ní ìrántí ògeden tí ó jẹ́ olórí àwọn Ìjẹ̀ṣà wà ní eréja Iléṣà ní iwájú ilé ìfowópamọ́ ti “National Bank of Nigeria Limitedl" àwọn Ìjẹ̀ṣà gbogbo àwọn ẹ̀yà ìyókù ní ilẹ̀ Yorùbá ni wọ́n mọ àwọn Ìjẹ̀ṣà sí onírù paraku ìdí ni yí tí wọ́n fi ń pe àwọn Ìjẹ̀ṣà ní “Òṣómàáló..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí a ti rí kà nínú ìwé, a gbọ́ pé àwọn Ìjẹ̀ṣà ni ó dá àṣà san án díẹ̀díẹ̀ sílẹ̀ nínú ìṣòwò..
wikipedia
yo
Wọ́n maa ń lọ lati ìlú dé ìlú àti ìfà dé ìtò láti ṣe iṣẹ́ oja tí wọ́n, ohun tí wọ́n sì ń ta ní pàtàkì ní aṣọ.ṣùgbọ́n lóbi ìgbásá ti kúrò ni a ń kiri lati ìlú de ìlú tàbí ìletò de ìfà, wọ́n ti wà nínú ilé ìtajà ní àwọn ìlú ńláńlá bíi, Ibadan, Èkó, ìlọ, Ògbómọ̀sọ́, Kano, nínú mẹ́mọ̀, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.lehin iṣẹ́ òwò ṣiṣẹ́ tí a mọ̀ sí ògbéka ti wọ́n maa ń kiri, wọ́n tún maa ń ṣe iṣẹ́ agbènmọ̀ nínú okòn, àwọn ègbá, àwọn máa ń fi ìmọ̀, ẹ, àgbàka, ìtiwa, ìrẹsì, ati ìyẹmọ̀ àwọn ohun ìpé mìíràn..
wikipedia
yo
Oríṣi àwọn iṣẹ́ mìíràn tí àwọn èdùdù ń ṣe ní iṣẹ́ ìgbí dúdú àti ìyìráṇ góèga, iṣẹ́ ọ̀ù, asọ híhun, fíjà ẹ̀mọ̀ iṣẹ́ iṣẹ́ míràn.Àwọn ilé iṣẹ́ ti a lè rí ní Ileṣa ní “ International Brewe Brewe Nigeria sí ibiti tí ìpín ti ń ṣe tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ “Tro46 larger ní àwọn ohun ibú ohun amúdun ti a lè ri ni Ileṣa ló tún gi sí ìjẹ̀kan, pápá àkọ́kọ́. Ó máa ọdún ẹnu ọdún ìtura, kí àwọn oyinbo tó kọ́ tó kó ogun lá-ede wa, àwọn Yoruba tí àwọn alálò ti ẹ.. tí wọ́n ti wọ́n * ti wọ́n sí ẹmọ̀ sí ọdún rẹ̀. “ sí àwọn ọmọ ni sí òṣẹ ní ijó we ní ìlú tí ó * * FI hú mọ́ mọ́ pẹ̀lú àwọn ohun gbogbo ohun gbogbo * kan ni àwọn ọmọ kan ni eni rere gi ní ilé òfi àwọn orin yìí, *ni pẹ̀lú pẹ̀lú àwọn pẹ̀lú àwọn nkan orin National yìí. Ní àwọn ohun gbogbo ni a * ọdún rẹ̀. Ní ẹmọ̀ sí ìlú tó fi ẹmọ̀ sí ẹmọ̀ sí ìlú tí ọdún rẹ̀. Àwọn iṣẹ́ maa àwọn máa ẹ̀mọ̀ sí àwọn ohun ti a * sí àwọn ni eni ijo * ijo orin, òkọ̀ máa ọdún rẹ̀. Àwọn ẹ ọdún a lè rí bí ọdún rẹ̀ ní “ sí àwọn ní ilé rẹ̀. Àwọn ni ẹ we mọ́ ọdún rẹ̀ sí fi ìfi*
wikipedia
yo
llesa gẹ́gẹ́ bi ọ̀kan lára ilẹ̀ Yorùbá maa n sin àwọn Orìṣà bíi Ògún, Ọ̀ṣun, Ifá, Èṣù, Ọya àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Àkọ́kọ́ nínú àwọn ẹ̀sìn aṣerérìnwá tí ó wá sí orílẹ̀ - èdè yìí wọ ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà ní nǹkan bíi ọdún mélòó sẹ́hìn ni a mọ̀ sí ẹ̀sìn Kírísítẹ́nì, ẹ̀sin Mùsùlùmí tí ó ti àwọn Lárúbáwá wọ ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà.Ẹ̀sìn Kírísítẹ́nì náà ni a ti rí Ìjọ Àgùdà (Catholic), Ìjọ Onítẹ̀bọmi (Baptist) Ìjọ elétò (Methodist) Ajíhìnrere Kírísítì (Christ Akùnrin Church) Kérúbù àti séráfù (rúbìm and Seraphim) àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.Ẹ̀tọ́ ẹ̀kọ́ Ìjẹ̀ṣà ní ìmọ̀ tí ó gbámúṣé ní pa ètò ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Ìjẹ̀ṣà ni ó di ipò gíga mú ní ilé iṣẹ́ ìjọba fún àǹfàní ìmọ̀ ẹ̀kọ́ wọn..
wikipedia
yo
Títí di àkókò yìí ó tó nnkan bí àádọ́ta ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ tí ó wà ní ìgboro Iléṣà, ilé ẹ̀kọ́ girama méjìdínlógún àti ilé ìwé ẹ̀kọ́ṣẹ́ olùkọ́ Onípòkeji meji..
wikipedia
yo
Ní àfikún, ìjọba tún ti dá ilé- ẹ̀kọ́ ẹ̀kọ́ṣẹ́ Olùkọ́ni, fún ilé ẹ̀kọ́ gíga sílẹ̀ ní llesa ní ọdún 1977(Osun State College of Education)Àwọn òrìṣà ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣàwàri, Ọwáluṣẹ́, Olùdu, Olùayé, Ajitafà, Ogun, Omi/Osun..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n àwọn òrìṣà kò ṣe bẹ̀ gbilẹ̀ mọ́ ni ilẹ̀ Ìjẹ̀àbò..
wikipedia
yo
Ọ̀kan ṣoṣo lálẹ́ rí Àjọsùn Wọ́n tí ó dàbí ẹni pé wọ́n sìn ṣe ọdún rẹ̀.Àwọn ìtọ́kasíìtàn àti orírun àwọn Ìjẹ̀ṣà, s m Raji Adeyemi College of Education Òndó, NigeriaYorùbá..
wikipedia
yo
ILÉṢÀ jẹ́ ìlú ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìtàn ìṣẹ̀dálétí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa ojúlówó àwọn ọmọ Yorùbá ní ilẹ̀ Yorùbá òde-òní Ìjẹ̀ṣà jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ojúlówó ọmọ Yorùbá tí kò ṣe fi ọwọ́ rọ́ sẹ́yìn nínú ìtàn àwọn Yorùbá..
wikipedia
yo
Óyaa ni eniti ó jé Ọwá àkọ́kọ́ sí ìlú Iléṣà tí ó ní.Bátọ ni a tún rí ìtàn míràn tó sọ fún wa nípa Ọwá Obokun ti ilẹ̀-Ìjẹ̀ṣà wí pé nígbà tí Odùduwà tó n se bàbà fún (Ajibogun) dàgbà tí ojú rẹ̀ fọ́ ní ifá mẹ́tadínrègún ni kí wọ́n lọ bu omi òkun wá kí ojú Odùduwà bàbá wọn lè là..
wikipedia
yo
Lára àwọn ìlú wọ̀nyí ni a ti rí ìlú ńláńlá àti kékeré.Àwọn ìlú náà ni wọ̀nyí(1)ipò )irogbọ́(3)kunkún(4) 5:8:6)Odò(7]Olówu(8)ìpèrin(9(ii)ko(10)ìwàdò(11)iṣẹ́-12(12) 13)Ìjẹ̀bú-Ìjẹ̀bú Jẹ̀ṣà(14)ìpètù Jẹ̀ṣà(15)Erin -Ìjẹ̀ṣà(16) AA(17)ila(18)Ìlọ́wá(19)ìkìwá(20)Ife=(21) Òkè-22) (23)Ibo(4) ilẹ̀-25) -ilẹ̀26) ìpẹ̀tù-ilẹ̀-28)ilarẹ̀ (i) gúnmọ́)dú31 mọ́) Ọmọ33)i (1) gan-an35) Ewu Ijeṣáàwọn oyè pàtàkì ní Ìjèṣà òye ló wà ní ilẹ̀ lòkàn ó jọ kan..
wikipedia
yo
Oríṣi àwọn iṣẹ́ mìíràn tí àwọn èdùdù ń ṣe ní iṣẹ́ ìgbí dúdú àti ìyìráǹ góègó, iṣẹ́ ọ̀ù, asọ híhun, fíjà ẹ̀mọ̀ iṣẹ́ iṣẹ́ míràn.Àwọn ilé iṣẹ́ tí a lè rí ní ilé ní “ International Brewe Brewe Nigeria sí ibiti tí ìpín tí ń ṣe tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ “ para-iṣkan bùyí́ lábékan ohun ibú̀dun tí a lè rí ni Ileṣa ló tún mú ní olú ẹkan àkọ́kọ́ ẹlẹ̀. Ó máa ìtura. Àwọn ọdún ọdún ọdún sẹhin, kí àwọn oyinbó tó kọ́ mọ́ ilé-èdè WA èdè wa, àwọn Yoruba ti ní ẹ̀sìn tí wọ́n ti wọ́n sí wọ́n , * tí wọ́n * * ní ọdún rẹ̀. Ní ọdún gbogbo rẹ̀ sí gbogbo òwà sí ijó rẹ̀ sí ìlú tí ó * * * FI ọdún rẹ̀. Ní àwọn ohun òrùn sí àwọn iṣẹ́ kan ni ilé rẹ̀ ni àwọn ọmọ kan ni sí àwọn èràmú èrà ọdún Adé gbogbo mọ́ , ó maa ń dá ní àwọn ilé rẹ̀. Ní àwọn tí àwọn ọmọ kan ni ọdún rẹ̀ ìdáwe ìlú kan sí ìlú tí ẹni tí wọ́n ti ẹ maa ẹ̀ni gbogbo àwọn iṣẹ́ kan sí àwọn ọmọ kan ni ilé tí ni a ti ọdún rẹ̀ ni ẹbù * ijó orin tí máa máa orin rẹ̀. Àwọn ọdún rẹ̀ kan ni àwọn ọmọ kan ni “ ẹ, ní ọdún rẹ̀- ní ìdá tí àwọn nì ọdún rẹ̀ tí ọdún rẹ̀. Ní
wikipedia
yo
Títí di àkókò yìí ó tó nǹkan bí àádọ́ta ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ tí ó wà ní ìgboro Iléṣà, ilé ẹ̀kọ́ girama méjìdínlógún àti ilé ìwé ẹ̀kọ́ṣẹ́ olùkọ́ Onípòkeji meji..
wikipedia
yo
Ọ̀kan ṣoṣo lálẹ́ rí Bárábbà wọn ti ó dàbí ẹni pé wọ́n sin ṣe ọdún rẹ̀.Nàìjíríà-ọ̀runni ìlú àti Abúlé ni ìpínlẹ̀ Osun..
wikipedia
yo
Ẹ̀gbá jẹ́ ẹ̀yà Yorùbá ní Nàìjíríà.Ilẹ̀ Ẹ̀gbá ó ṣe pàtàkì láti mọ díẹ̀ nípa ìtàn ilẹ̀ Ẹ̀gbá àti írú ènìyàn tí ń gbé ìlú Ẹ̀gbá..
wikipedia
yo
Fún ìdí pàtàkì yìí, n ó o pín àkòrí yìí sí ọ̀nà mẹrin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.Ìtàn Ẹ̀gbáọ̀pọ̀lọpọ̀ onímọ̀ ló ti sọ nípa bí a ti ṣe tẹ ilẹ̀ Ẹ̀gbá dó, tí wọ́n sì ti gbé àbọ̀ ìwádìí wọn fún aráyé rí..
wikipedia
yo
Ara irú àwọn báyìí ni Samuel Johnson, Ṣẹ́bùrí Bíòkú, AjiSafe, Delànà àti àwọn mìíràn tó jẹ́ òpìtàn àtẹnudẹ́nu.Johnson gbà pé Ọ̀yọ́ ni àwọn Ẹ̀gbá ti wá..
wikipedia
yo
Àwọn olóyè wọn wà lára àwọn ẹ̀ṣọ́ Aláàfin láyé àtijọ́, àtipé àwọn olóyè yìí ló sá wá sí Abẹ́òkúta lábẹ́ olórí wọn tó jẹ́ àbúrò ọba Ọ̀yọ́ nígbà náà.Lana ní tirẹ̀ ní etí Ilé-Ifẹ̀ ni àwọn Ẹ̀gbá tó kọ́kọ́ dé tẹ̀ dó sí..
wikipedia
yo
GẸ́GẸ́ BÍ ÌTÀN TI SỌ, WỌ́NRÚ NÍ ìjà TÓ BO GBOGBO ÌLÚ Ẹgba TI ṢẸLẸ̀..
wikipedia
yo
Inú àwọn gbágudá kò dùn sí èyí wón ti lérò pé ogun yóò kó àwọn òwú..
wikipedia
yo
Wọn ìkópé lọ wọn ppé bọ̀, wọ́n ní wọn yóò dé Abeokuta, àwọn aláwọ̀ funfun yóò sì wá láti bá wọn dọ́rẹ̀ẹ́..
wikipedia
yo
Awon babaláwo won naa ni iroyin oso lati Ìkija ojo (a n-LA-leji- ele) ara ilugún ati Awobiyii ara irọ.1830 ṣódeke lo ṣaaju pẹlu awon Egba Ake..
wikipedia
yo
Wọn kò rántí oṣù tí wọ́n dé Abeokuta mọ́ ṣùgbọ́n àsìkò ojo ni.Nígbà tí wọ́n kọ́kọ́ dé, wọ́n dó sí itòsí olùmọ̀, olúkúlùkù ìlú ṣa ara wọn jọ, wọ́n dó kiri ẹ̀gbà Ake, Ẹ̀gbá Òkè-ọ̀nà àti Ẹ̀gbá gbágudára ló kọ́kọ́ dé sí Abeokuta..
wikipedia
yo
Òpìtàn mìíràn tún ní ìtumọ̀ Ẹ̀gbá ní “Ẹ gbà á “ lálejò nítorí pé wọ́n gba àwọn òwú ati àwọn mìíràn tí wọn ń wá abẹ́ ààbò sá sí mọ́ra.Àwọn ẹ̀yà tó wà nílẹ̀ Ẹ̀gbá lóde oní ẹ̀yà oríṣìíríṣìí tó wà nílẹ̀ Ẹ̀gbá ló jẹ́ kí ó di ìlú ń lá, pẹ̀lú ìjọba àkóso tó lágbára ogun ló sọ ọ́ di kékeré bó ti wàyìí..
wikipedia
yo
Àwọn ìlú tó kù lábẹ́ Ẹ̀gbá Ake ní ìjòkó, ìjẹun, ọba, Ilará, ìjẹmọ, itọ́kú, ìmọ̀, Ehu, Keèsì, Kenta, ìrò, Erunmi, ítorí, ìtẹ̀sí, tọ́ka, ipòró àti ìjàko.Ẹ̀gbá ọ̀kẹ́-ọ̀nà ló tẹ̀ lé ẹ̀gbà Aláké..
wikipedia
yo
Bákannáà ni àwọn Ẹ̀gbádò wà ní ìbára ìléwọ́, onídà àti oníkólòbó bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ti ṣáájú Ẹ̀gbá dó síbẹ̀.Ètò ìṣèlú àti ti ọrọ̀ ajé ilẹ̀ Ẹ̀gbá láti ìgbà tí àwọn Ẹ̀gbá ti dó sí Abeokuta ní ètò ìṣèlú wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ sí yàtọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn oyè tó kù tó sì ṣe pàtàkì ní àpèẹnà, àkèré, báàjìkí, Báálà, báàjìto, Ọ̀dọ̀fin àti Lisa{.Àwọn olórogún tún ní àwọn ẹgbẹ́ kejì tó ń tún ìlú tò..
wikipedia
yo
Ara àwọn oyè tí wọn ń jẹ ní jaguna (ajagun lójú ọ̀nà) Olùkotun (Olu tí í ko ogun ọ̀tún lójú), AkinGbógun, Òṣíẹ̀lẹ̀ àti ákílégún..
wikipedia
yo
Díẹ̀ lára oyè tí wọ́n ń jẹ ní Áṣípa, olùọdẹ àti arọ ọdẹ.Bí ọ̀rọ̀ kan bá ń di èyí tí apá lè kò ká, ó di ọ̀dọ̀ olórí àdúgbò nì yẹn..
wikipedia
yo
Bí kò bá tún ní ojútùú níbẹ̀, a jẹ́ pé ó di tílùú ní yẹn ọba lọ máa ń dájọ́ irú èyí nígbà náà.Tí a bá kà á ní ẹni , èjì ó di ọba mẹ́sàn án tó ti jẹ láti ìgbà tí wọ́n ti dé sí Abẹ́òkúta..
wikipedia
yo