cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ọkàn nit i apa ila oorun ti wọn gbe le ori eka-ede ti won n so ni, Ipinle SVan..
wikipedia
yo
Ekeji nit I ìwọ̀-oòrùn tí wọn gbé lé orí ẹ̀ka-èdè tí wọn ń sọ ní islanbul..
wikipedia
yo
Eléyìí ni wọ́n ń sọ ní orílẹ̀-èdè Turkey.Àwọn ìtọ́kasíàwọn èdè..
wikipedia
yo
Armenia (; , sísọ̀ háyàStan, ), fún iṣéọba bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ilẹ̀ Armenia (háyàStani Hanramímọ̀wyọ`4] háyà Hanra·rapetut'yún, ), jẹ́ orílẹ̀-èdè òkè-ilẹ̀ ti ilẹ̀ yíká ní agbègbè kátúmọ̀f ní Eurasíà..
wikipedia
yo
Ó bùdó sí orítamẹ́ta apáìwọ̀òrùn Asia àti apáiọ̀run Europe, ó ní bóde mọ́ Túú ní ìwọ̀òrùn, Georgia ní àríwá, dé facto Nadi-Khkh Republic alómìnira àti Azerbaijan ní Ilaọrun, àti ìran àti ilẹ̀ Azer Nakh NAchivan ní gúúsù. Àwọn orílẹ̀-èdè Europeàwọn orílẹ̀-èdè Asia..
wikipedia
yo
Argentinaninu ètò ìkànìyàn 1995, iye àwọn ènìyàn tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Ajẹntínà (Argenti-àná) lé díẹ̀ ní mílíọ̀nù mẹ́rìnlélógójì àti àti ààbọ̀ (46 245 66–)..
wikipedia
yo
Èdè Panyan-an ní Èdè tí wọ́n fi n ṣe Ìjọba ní ibẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn èdè mìíràn tí wọ́n tún ń sọ ní orílẹ̀-èdè yìí lé ní ogún..
wikipedia
yo
Lara awon ogun ede yii ni awon ede ti won n pe ni AmeriDiana (Ameridian languages) wa..
wikipedia
yo
AméDiana yìí ní ‘Áránì, Fhícanian, mẹ́tàco àti Quechua
wikipedia
yo
Àwọn èdè tí ó tún wà lára ogún yìí ni èdè tí àwọn tí ó wá ṣe àtìpó ń sọ..
wikipedia
yo
Lára wọn ni Èdè ìtíli (Ìtahan) àti Jámánì (Herman)..
wikipedia
yo
Èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbilẹ̀ sí i ni orílẹ̀-èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè fún ọwọ́ àgbáyé àti èdè àwọn tí ó ń ṣe àbẹ̀wò wá sí ibẹ̀ (International Trade and Tourism)..
wikipedia
yo
Wọ́n n lo èdè Gẹ̀ẹ́sì yìí pẹ̀lú èdè Phán-an.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń sọ èdè yìí tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà igba ní Iraanu (Ìran) àti Ìráàkì (Iraq) pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn mìíràn tí wọ́n tún ń sọ ọ́ ní Àárín Gbùngbùn Ìlà-Oòrùn Àgbáyé (Middle Tast)..
wikipedia
yo
Láti Ṣetúrì Kẹfà ni wọ́n ti ń fi Árámáíkì àtijọ́ (Classical Aramaic) kọ nǹkan sílẹ̀ ní àárín gbingbein ila-oorun agbaye (Middle East)..
wikipedia
yo
HeBẹ́ẹ̀rù ni ó wà gba ipò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí èdè tí àwọn Juu ń sọ.Ẹ̀ka-èdè ìwọ̀-oòrùn èdè yìí (Western Dialect) ni èdè ti jẹ́Èṣù Kristi àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ń sọ..
wikipedia
yo
Ẹ̀ka-èdè kan tí ó wá láti ara ẹ̀ka-èdè yìí ni wọ́n sì ń sọ ní àwọn abúlé kan ní ilẹ̀ Siria àti Lẹ́ófóònù.Ní nǹkan bíi Chinaẹ́ńtúrì keje ní èdè Lárúbáwá gba ipò èdè Árámáíkì..
wikipedia
yo
Ẹ̀ka-èdè apá ìwọ̀-oòrùn èdè yìí tí à ń pè ní Síríákì (syricac) ni àwọn Ìjọ Àgùdà ara Firiaki (Syriac Catholic) ń lọ..
wikipedia
yo
Èdè yìí sì ṣe pàtàkì nítorí pé láti ara rẹ̀ ni Hebeeru, Lárúbáwá àti àwọn èdè mìíràn ti dìde.Ìtọ́kasí àwọn èdè..
wikipedia
yo
Èdè Lárúbáwá tabi èdè Áráàbùara Ede ṣẹ̀mítíìkì ní èdè Árábíìkì (Arabic (èdè ṣètòbàáwa))..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń sọ ọ́ tó mílíọ̀nù lọ́nà igba gẹ́gẹ́ bí èdè abínibí ní àríwá Arikarika àti ìlà-oòrùn-gúsù EETAsia (àsíá)..
wikipedia
yo
Àìmọye ènìyàn tí a kò le fi ojú da iye wọn ni ó ń sọ èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè kejì, ìyẹn èdè àkọ́kún-tẹni ní pàtàkì ní àwọn orílẹ̀-èdè ti ẹ̀sìn kúmulúmù ti gbilẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó lọ ṣe àtìpó ní pàtàkì ní ilẹ̀ Faransé náà máa ń sọ èdè yìí..
wikipedia
yo
Ibi tí àwọn tí ó ń sọ èdè yìí pọ̀ sí jù ní Algeria, Egypt, Iraq, Morocco, Saudi Arabia, Sudan, Syria, Tunisia àti Yeman..
wikipedia
yo
àwọn ẹ̀ka-èdè rẹ̀ kan wà tí ó jẹ́ ti apá ìwọ̀-oòrùn tí àwọn kan sì jẹ́ ti ìlà-oòrùn..
wikipedia
yo
Èdè ti a fi kọ kọ́raanu silẹ ni a n pe ni 'Classical' tabi 'Literary Arabicoṣù
wikipedia
yo
Èdè mímọ́ ni gbogbo ṣulúmù àgbáyé tí ó tó ẹgbẹ̀rún ó lé ọgọ́rùn-ún mílíọ̀nù ní àgbáyé (1, 100 million) nínú ètò ìkànìyàn 1995 ni ó mọ èdè 'Classical Arabic' yìí..
wikipedia
yo
Olórí ẹ̀ka-èdè Lárúbáwá wà tí ó sún mọ́ èyí tí wọ́n fi kọ Koraanu..
wikipedia
yo
Oun náà ni wọn sì máa n lọ dípò àwọn ẹ̀ka-èdè Larubawa..
wikipedia
yo
Pupọ ninu àwọn tí ó ń ṣọ́ ẹ̀ka-èdè Lárúbáwá yìí ni wọn kò gbọ́ ara wọn ní àgbọ́yé..
wikipedia
yo
mejidinlọgbọn ni àwọn álúfábẹ́ẹ̀tì èdè Àwabrúbọwà..
wikipedia
yo
Odi ọ̀tún ni wọ́n ti fi ń kọ̀wé wá sí apá oṣù yàtọ̀ sí àlùfãkan ti Romaãnú, ti Lárúbáwá ni àwọn ènìyàn tún ń lò jù ní àgbáyé..
wikipedia
yo
A ti rí àpẹẹrẹ pé láti nǹkan bíi Senteri kẹta ni a ti n fi èdè Lárúbáwá kọ nǹkan sílẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí ẹ̀sìn mú`lumi de ní Britúrì keje ni ọkọsílẹ̀ èdè yìí wá gbajúgbajà..
wikipedia
yo
Wọ́n tún wá jí sí ètò ìkọ̀sílẹ̀ èdè yìí gan-an ní sétúrì kọkàndínlógún nígbà tí ìkọ̀sílẹ̀ èdè yìí ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ará..
wikipedia
yo
Ní pẹ̀lẹ́-n-pẹ̀lẹ́ ní èdè yìí pín sí (ìyẹn ni pé eléyìí tí olówó n sọ lè yàtọ̀ sí ti Talika tàbí kí ó jẹ́ pé eléyìí tí obìnrin n ló lè yàtọ̀ sí ti ọkùnrin).Àwọn ìtọ́kasíàwọn èdè..
wikipedia
yo
Antibubu ati BarBuda (; SPAN fun “atijọ” ati “onírùngbọ̀n") jẹ iṣ a Twin-ede Erékùṣù-meji larin omi-okun KariZulu ati Okun Atlantiki..
wikipedia
yo
O ni Erekusu meji níńlá ti awọn eniyan dójú bẹ, antibubu ati BarBuda, pẹlu awọn erekusu kekeke melo kan (bi awọn Erékùṣù Great bird, Green, Guinea, Long, mọlé ati York).itọkasi..
wikipedia
yo
Ìgbèríko òde Filistiniju ní bodè mọ́ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ilẹ̀ Kóńgò àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú Ilẹ̀ Kóńgò.Ìtàn Angola di iléàmúsìn Portugal ní 1884 Lẹ́yìn Ìpàdé Berlin..
wikipedia
yo
Kò pẹ́ lẹ́yìn ìlọ́mọlọ́mọ ní ogun abẹ́lé ṣẹlẹ̀ láti 1975 dé 2002..
wikipedia
yo
Angola ni ọ̀pọ̀ àlùmọ́nì àti Petroliọmú, Be sìni okòwò rẹ̀ ti úngbéra sókè pẹ̀lú ìwọ̀n ẹyọìka méjì láti ọdún 1990, àgàgà látẹ̀yìn ìgbà tí ogun abẹ́lé wá sópin..
wikipedia
yo
Síbẹ̀síbẹ̀ ọ̀págun Ìjàyè ṣì kéré gidigidi fún ọ̀pọ̀ alábùgbé, bẹ́ síni ọjọ́ orí àti iye ọ̀fọ̀ ọmọwo ní Angola jẹ́ àwọn èyí tó burú jùlọ lágbà.Jeografi-okòwò ìtọ́kasí Angola..
wikipedia
yo
AnDora tabi fun iseoba O je ile-ọmọba Andorra, bakanna won tun mo si ile-ọmọba awon Àfonífojì ile anDora (Principality of the Valleys of Andorra) je orile-ede Alafiléyika ni apa guusuiwoorun Europe..
wikipedia
yo
Ninu ètò ìkànìyàn 1995, àwọn tí ó ń gbé anDora jẹ́ ẹgbẹrun meji-dún-láàádọ́rin (68,000)..
wikipedia
yo
Àwọn èdè tí ó jẹ́ ti ìjọba níbẹ̀ ní kaàhanu tí ìpín ọgọ́ta nínú ọ̀gọ́rùn-ún n sọ (60%) àti èdè Faransé..
wikipedia
yo
Wọ́n tún n so Ksitilianu tí àwọn Panyan-an-an gan-an fún ọwọ́ agbaye àti láti fi bá àwọn tí ó bá wá yẹ ilú wọn wó soro . AnDorad..
wikipedia
yo
''Amorite’’ jẹ́ èdè semitiiki (Semitic) kan ni amoraiti (Amorite) tí wọ́n ń sọ ní agbègbè àríwá Síríà (Syria) òde òní ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún méjì ọdún sí ẹgbẹ̀rún kan àbọ̀ sáájú ibi Kírísítì..
wikipedia
yo
Díẹ̀ ni a mọ̀ nípa èdè yìí nítorí pé láti inú orúkọ ènìyàn àti àwọn àkọsílẹ̀ díẹ̀ tí a rí tí wọ́n ọpẹ́ sí ara òkúta nìkan ni a mọ̀ nípa èdè yìí..
wikipedia
yo
Amhariki èdè semitiiki (Semitic) kan ni eléyìí ti nǹkan bu mílíọ̀nù márùndínlógún ń sọ gẹ́gẹ́ bí èdè àkọ́kọ́ ní ethopia (itopia)..
wikipedia
yo
Àwọn bu mílíọ̀nù márùn-ún ni ó ń sọ èdè yìí ní agbègbè Ethiopia nígbà tí àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíọ̀nù mìíràn ń sọ èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè kejì àkọ́kúntẹnu ní Ethiopia àti Sudan (Sunígbàtí)..
wikipedia
yo
Láti nǹkan bíi sétúrì kẹrinla (14th century) ní èdè yìí ti ní àkọsílẹ̀..
wikipedia
yo
Àkọtọ́ yìí ni kọ́ńṣónáǹtì mẹ́tàlélọ́gbọ̀n ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì ní ẹ̀dá méjeméje..
wikipedia
yo
Ẹ̀dá kọ́ńsónáǹtì tí ènìyàn yóò mú lọ dúró lọ̀rọ̀ fáwẹ́lì tí kọ́ńsónáǹtì náà yóò bá jẹ yọ..
wikipedia
yo
Awon kan si ti kora won jo fun ipolongo lati so ede yii di àjùmọ̀lò (Standarnítì). awon ede..
wikipedia
yo
AnGuilla nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn ènìyàn tó wà ní AnGuilla jẹ́ ẹgbẹ̀rún méje àti ọgọ́rùn-ún (7,100)..
wikipedia
yo
Pupọ ninu àwọn eniyan ibẹ̀ ni wọ́n ń sọ èdè kirio tí wọ́n gbé ka èdè Gẹẹsi (English based Creole)..
wikipedia
yo
kirio yìí ni ó wọ́pọ̀ jù ní antileesi (Nolu Antilles)itọkasi àwọn agbègbè okere Britani..
wikipedia
yo
Olódùmarè káàkiri àgbáyé ni a ti mọ̀ pé Olódùmarè wà, ẹni tí ó dá ayé àti ọ̀run àti ohun gbogbo ti ń bẹ nínú wọn òyígíyigì ọba àìrí Arínú-ròde olùmọ̀ràn ọkàn, Alèwílèṣe, Aleselewi, ọba àtẹ̀lé bí ẹni tẹni, Ọba àtẹ̀sánmọ̀ bí ẹni tẹ̀ṣọ, Ọba lónìí, Ọba lọ́la, Ọba títí ayé àìnípẹ̀kun, Olówó gbogbogbò ti ń yọmọ rẹ̀ nínú òfin, Ọba olójú lù kára bí ajere, Ọba onínú funfun àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Èyí ni pé oríkì Olódùmarè pọ̀ lọ jàkà, bí a bá sì gbọ́ tí àwọn Yorùbá bá sọ pé ‘Orí mi o tàbí ọlọ́jọ́ òní o, Olódùmarè ni wọ́n ń pè ní orí, èyí tí ó dúró fún Ẹlẹ́dã Orí àti ọlọ́jọ́ òní tí ó dúró fún ẹni tí ó ní ọjọ́ òní..
wikipedia
yo
Tàbí nígbà mìíràn tí àwọn Yorùbá bá rí ohun tí ó ya ni lẹ́nu wọn a ni ‘Baba o’ èyí tí ó dúró fún Olódùmarè.Àwọn ọmọ ènìyàn gbà wí pé Ọlọ́run tóbi ju gbogbo ẹ̀dá lọ ó sì jẹ́ ẹni tí wọ́n gbọdọ̀ má a bọlá fún, èrò ọkàn àwọn Yorùbá ni pé Ọlọ́run tàbí Olódùmarè tóbi púpọ̀, ó sì ju ẹnikẹ́ni lọ àti nítorí èyí kò yẹ kí wọ́n máa dárúkọ mọ́ ọ lórí bí wọ́n ti ń ṣe sí ẹ̀gbẹ́ àti ọgbà wọn, láti bu ọlá fún-un àti láti fi ìtẹríba wọn hàn fún un wọ́n ń fi iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ pè é, wọn a ní ẹlẹda, èyí ni ẹni tí ó dá ọ̀run, àti ayé, òyígíyigì, èyí ni ẹni tí ó tóbi tóbẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ tí kò sí ohun tí a lè fi wé wé..
wikipedia
yo
Ọba àwámár, èyí ni ẹni tí a kò lè rí ìdí iṣẹ́ rẹ̀, alabaláṣẹ, èyí ni ẹni tí ó ní Aba àti àṣẹ, Baba, èyí ni Baba gbogbo ẹ̀dá inú ayé, Ọ̀gá ògo; èyí ni Ẹni tí ó ni ọ̀run èyí tí ó jẹ́ ògo ẹ̀dá tàbí nígbà mìíràn a lè túmọ̀ rẹ̀ sí ẹni tí ògo tàbí ìgbéga ẹ̀dá ń bẹ ní ọwọ́ rẹ̀, atẹ́rẹrẹ, èyí ni ẹni tí ó tóbi, tí ó sì ni gbogbo ayé ní ìkáwọ́ rẹ̀, ẹlẹ́mìí, èyí ni ẹni tí ó ni ẹ̀mí ẹ̀dá..
wikipedia
yo
Bí a bá tún gbọ́ nígbà mìíràn tí àwọn àgbàlagbà ń lo àwọn ọ̀rọ̀ bíi ‘Ègun tàbí wọ́n ń lo àwọn ọ̀rọ̀ bíi ‘Olú’ Olódùmarè kan náà ni wọ́n ń tọ́ka sí..
wikipedia
yo
Ohun tí wọ́n ń tọ́ka sí nínú gbólóhùn yìí nipé ẹ ẹni tí Olú, èyí tí ó dúró fún Olódùmarè “Bá ti dá àyànmọ́ kan mọ́ ẹnìkan, a kò lè fara wé irú ènìyàn bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Adùn ún ṣe bí ohun tí Olodumare lọ́wọ́ sí, asọ̀rọ̀ ò ṣe bí ohun tí Olodumare kò lọ́wọ́ sí, Alèwílèṣe, ÀṣẹkànMaku..
wikipedia
yo
Ìgbà mìíràn a tún lè sọ pé Ọlọ́run nìkan ló gbọ́n, ó rí ohun gbogbo, ó sì lè ṣe ohun gbogbo, arínúróde olùmọ̀ràn ọkàn, Yorùbá sọ pé “amòòkùn sọlẹ́ bí Ọba ayé kò rí, Ọba ọ̀run ń wò ó, èyí túmọ̀ sí wí pé kò sí ohun tí a ṣe ní ìkọ̀kọ̀ tí Olódùmarè kò rí, kedere ni lójú Olódùmarè, àwọn òrìṣà ló máa ń jẹ́ àwọn arúfin ní ìyà ṣùgbọ́n Olódùmarè ló máa ń dájọ́ fún wọn, fún àpẹẹrẹ ní ìgbà kan gbogbo òrìṣà fẹ̀sùn kan Ọ̀rúnmìlà níwájú Olódùmarè lẹ́yìn tí tọ̀tún tòsì wọn rọ̀jò Olódùmarè dá Ọ̀rúnmìlà láre, odù ifá kan jẹ́rĩ sí eléyìí, odù náà lọ báyìí “Ọ̀kan kì í jẹ́ ká mọ nǹkan pínpín, Adia fún òdú..
wikipedia
yo
mẹ́rìndín lógun níjọ́ tí wọ́n ń jìjà àgbà relé Olódùmarè, nígbà tí àwọn ọmọ irúnmọlẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rindínlógún tán ń jíjà ta ni ẹ̀gbọ́n ta ni àbúrò láàárín ara wọn, wọ́n kẹjọ lọ sọ́dọ̀ Olódùmarè, níkẹyìn, Olódùmarè dá ejò pé èjìǹ ni àgbà fún àwọn ọdú yókù..
wikipedia
yo
Yorùbá gbàgbọ́ pé onídájọ́ òdodo ni sẹ́dua, ìdí nìyí tí Yorùbá fi ń sọ pé Ọlọ́run mú u tabi ó wà lábẹ́ pàṣán ‘Olodumare..
wikipedia
yo
òyígíyigì ọba ọ̀tá àìkú fẹ́rẹ̀kúfẹ́, a kì í sibẹsibẹ Olódùmarè..
wikipedia
yo
Igbagbọ Yorùbá ni pé bi àwọn angẹli ti jẹ́ olùrànlawo fún Olodumare lode ọrun ni àwọn oriṣa naa jẹ́ aṣoju rẹ lode iṣsalaye, àwọn òrìsà wọnyi jẹ alágbàwí àwọn eniyan níwájú Olodumare..
wikipedia
yo
A gbọ́ wí pé ìbáṣepọ̀ wà láàárín àwọn òrìṣà tàbí òòṣà ilẹ̀ Yorùbá àti Olódùmarè, àwọn Yorùbá gbàgbọ́ pé òòṣà wọ̀nyí ni wọ́n lè ran sí Olódùmarè yálà láti tọrọ nǹkankan lọ́wọ́ rẹ̀ tàbí dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀ fún ohun ribiribi tí ó ṣe fún wọn..
wikipedia
yo
Èrò yìí hàn ninu òwe Yorùbá kan pé “Ẹni mọ́jú Ọwá là ń bẹ Ṣówá, olójú Ọwá kan kò sí bíkòṣe ayaba”
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí ó fi jẹ́ pé bí a bá fẹ́ kí ọba ṣe ohun kan fún ni a ó bẹ ayaba sí i, ipò alágbàwí láàárín àwọn abọọ́ àti Olódùmarè ni àwọn òòṣà wa.Yorùbá..
wikipedia
yo
Ojú=Ìwé kìíníolóòfSãoń Olumibáyé M.Àwọn ẹbí èdè Khoisara ebi ètá KhoIsan yìí ni ó kéré jù lọ nínú àwọn ẹbí èdè gbogbo tí ó wà ní Áfíríkà..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí Greenberg (1963a) ti sọ, ó ní àwọn ni wọ́n dúró fún èyí tí ó kéré jù lọ nínú èdè Áfíríkà..
wikipedia
yo
Ìpilẹ̀ orúkọ èdè yìí a mú orúkọ yìí jáde láti ara orúkọ ẹgbẹ́ Khoi-ìtànun ti gúsù ilẹ̀ Afirika (South Africa) àti ẹgbẹ́ San (Bushmen) ti Namibia..
wikipedia
yo
A máa ń lo orúkọ yìí fún oríṣìíríṣìí àwọn ẹ̀yà tí wọ́n jẹ́ pé àwọn gan-an ni wọ́n kọ́kọ́ jẹ́ olùgbé ilẹ̀ South Africa kí àwọn Bantu tó wà, kí àwọn Òyìnbó ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì (Europe) sì tó kó wọn lẹ́rú.Oríṣìíríṣìí àwọn onímọ̀ ni wọ́n ti ṣiṣẹ́ lórí orúkọ yìí - KhoIṣan.Tan Gulmẹ́rìnlélógún àti Rainer Vossen ṣàlàyé nínú iṣẹ́ rẹ̀ pé Leonardt Schul 1928 1928 ni ó mú orúkọ yìí jáde láti ara Sttento’ tí ó túmọ̀ sí Khoi tí ó sì tún túmọ̀ sí ‘Person’ (Ènìyàn) àti ‘San’ tí ó túmọ̀ sí ‘Shger
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí ni onímọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ẹ̀dá àṣà, ìgbàgbọ́ àti ìdàgbàsókè ọmọnìyàn, Anthropologist Schapera (1930) tún wá fẹ́ orúkọ yìí lójú sẹ́yìn nípasẹ̀ 'hottentot'ati 'Bushman' gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà, (WIAIA) Àṣà (Cultural) àti ìmọ̀ ẹ̀dá èdè..
wikipedia
yo
Àwọn òrumo mìíràn tí wọ́n jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ẹgbẹ́ kẹta tí wọ́n tún ṣiṣẹ́ lé orúkọ yìí lórí ní Kólnlé (1975, 1981) Sands (1998) àti Trath (1980, 1986)..
wikipedia
yo
Wọ́n pinnu láti lo orúkọ náà KhoIṣan gẹ́gẹ́ bí olùborí fún àwọn èdè tí kìí ṣe ti Bantu tí kì í sì í ṣe èdè cusd..
wikipedia
yo
Àwọn onímọ̀ Ákíoloji fi hàn wí pé nǹkan bí ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́fà ọdún sẹ́yìn ni àwọn ènìyàn KhoIṣan ti fara hàn..
wikipedia
yo
Èyí fi hàn pé lọ́dọ̀ àwọn àgbà láéláé nìkan ni a ti lè máa gbọ́ èdè KhoIṣan nìkan báyìí..
wikipedia
yo
Bí èdè KhoIṣan tilẹ̀ farajọra ninu ètò ìró, gírámà tirẹ̀ yàtọ̀ gédégbé..
wikipedia
yo
Àìsí àkọsílẹ̀ ìtàn àwọn èdè wọ̀nyí mú kí ó nira díẹ̀ láti sọ ìfarajọra àwọn èdè yìí sí ara àti sí àwọn èdè adúláwọ̀ tí ó kù..
wikipedia
yo
Lóde àní, ilẹ̀ (South Western Africa) Gúsù-ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà títí dé aginjù Kalahari (Kalahari Desert), láti Angola dé South Africa àti ní apákan ilẹ̀ Tanzania nìkan ni wọ́n ti ń sọ Èdè KhoIṣan..
wikipedia
yo
Èdè Hadza ati Sandawe ni ilẹ̀ Tanzania ni a ṣáábà máa ń pè ní KhoIṣan ṣùgbọ́n wọ́n yàtọ̀ nípa ibùgbé àti ìmọ̀ ẹ̀dá èdè sí ara wọn..
wikipedia
yo
A wá lè sọ pé nínú gbogbo èdè àgbáyé, èdè KhoIṣan wà lára àwọn èdè tí àwọn onímọ̀ èdè kò kọbiara sí tí a kò sì kọ́ ẹ̀kọ́ nípa rẹ̀..
wikipedia
yo
Ipò tí èdè yìí wàèdè Khoìṣàn yìí gẹ́gẹ́ bí a ti sọ síwájú ń dín kù síi lójoojúmọ́ ni..
wikipedia
yo
Ohun tí ó fa èyí ni pé àwọn tí wọ́n ń sọ àmúlùmálà èdè KhoIṣan bẹ̀rẹ̀ sí í sọ èdè mìíràn tí ó gbilẹ̀ ní agbègbè wọn; wọ́n sì dẹ́kun kíkọ́ àwọn ọmọ wọn ní èdè abínibí wọn..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àwọn èdè wọ̀nyí ni kò ní àkọsílẹ̀ kankan tí ó sì fihàn pé sísọnù ti àwọn èdè wọ̀nyí sọnù, kò lè ní àtúnṣe..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ohun tí ó nira díẹ̀ láti sọ pé iye àwọn ènìyàn kan pàtó ni wọ́n ń so èdè KhoIṣan..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a kò mọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ ṣáájú kí àwọn Òyìnbó tó gòkè bọ̀, a kò sì mọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ ní gbogbo àkókò tí àwọn Òyìnbó ń ṣètò ìjọba, bẹ́ẹ̀ sì tún ni pé ìwọ̀nba la lè so mọ́ nípa ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní lọ́wọ́lọ́wọ́ yìí pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Ṣugbọn àkọsílẹ̀ fi hàn pé, ní bíi ẹgbẹrun ọdún meji sẹ́yìn, iye nọ́ńbà tí wọ́n kọ sílẹ̀ kò ṣeé tẹ̀lé mọ́; àkọsílẹ̀ sọ wí pé ẹgbẹrun lọ́nà ọgọfa sí ẹgbẹrun lọ́nà igba (120,000 - 200,000) ni wọ́n, ṣugbọn èyí ti di ohun àfìsẹ̀yìn bí eégún fi aṣọ..
wikipedia
yo
Díẹ̀ lára àwọn èdè KhoIṣan àti iye àwọn tí wọ́n ń ṣọ́ ọ..
wikipedia
yo
Egan, Iye àwọn tí ń sọ,ìlù, Sanhadare, 40, 000,Tanzania hailLo (San), 16,000,Namibia, Name (ekhoeìdámẹ́wàágo) 233,701701, Botswana, South Africa suua ,6,000,Botswana, tfìyà..
wikipedia
yo
5,000,Botswananeani ,1,000,BotswanaGánà, 2,000,BotswanakXO 10,000,Namibia, Angola, Botswana South Africa,Zambia//gwí, 2,500,Bówwananaro, 14,000,Botswana, Namibia =ikx'aull'Ein 2,000,Namibia, BotswanaKüng-Ketu,ka6,900900Botswana, Angola, South Africa.Ojú-ìwé Keji Ìhun Èdè KhoIsan Ìróàwọn Èdè KhoIṣan Kod Ti Ní ìfarajọra ninu ètò irọ..
wikipedia
yo
Ó dá yàtọ̀ gédégbé sí àwọn èdè ilẹ̀ Áfíríkà yòókù, ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè tí ó nira.FÁWẸ́LÌ Ọ̀pọ̀ àwọn èdè KhoIsan wọ̀nyí ni ó ń lo fáwẹ́lì márùn ún – /i// /ẹ/ /a/ /o/ tí/u tí a sì lè pè pẹ̀lú àwọn oríṣìí àbùdá wọ̀nyìí bíi, Ìranmú, (NASA) ìfi káà-ọ̀fun-pe (Pharyìbúṣọ́zation) àti oríṣìí àmúyẹ ohun bíi mímí ọ̀hún (Americanthy Voice) àti dídùn ohun © ti ti yóò sì mú bí i oríṣìí ìró ìró fáwẹ́lì bí i ogójì jáde..
wikipedia
yo
KóKógbè àti àwọn hadza tí ilẹ̀ Tanzania ń lo afẹ́yìn (dental ) afèrìgìpè (Alveọ̀lar) àti kílíìkì Aẹnu-gbé-ẹnu (LATẹraTẹra Clícks)..
wikipedia
yo
Pẹlu gbogbo àhesọ ọ̀rọ̀ títí di àkókò yìí orísun kílíìkì èdè KhoIṣan kò tíì yéni..
wikipedia
yo
“tsk” -kílíìkì afèrìgìpè - Ó máa ń dún bí ìgbà tí a bá ṣí ìdérí ìgò nípa gbígbé ahọ́n sí ẹ̀yìn ẹ̀yìn iwájú.-kí àfàjàtabàjálù - ó máa ń dún nípa gbígbé ahọ́n sílẹ̀ kúrò lára ajá ẹnu.-kilíìkì afẹ̀gbe-ẹnu-pé - ó máa ń dùn gẹ́gẹ́ bí irọ́ tí à ń lò lédè Gẹ̀ẹ́sì láti mú kí ẹṣin kánjú.-ki afètèpè máa ń dún nípa kíkanra ètè méjèèjì, tí a sì tún ṣí i sílẹ̀ ní kíá, gẹ́gẹ́ bí ìró ìfẹnukonu ni èyí ṣe máa ń dùn..
wikipedia
yo
Ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn kílíìkì wọ̀nyí ló lè ní kíkúnyún-un, (voicing) ríranmú (NASAlity), “faint” àti “Ẹ̀jẹ̀ction”
wikipedia
yo