cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Nínú oṣù yìí ni gbogbo àwọn Mùsùlùmí yóò ṣe ara wọn ní Òṣùṣù-ọwọ̀ tí wọn yóò sì kọ́ra dúró níbíi wúwo-Ma-nigeria-Mato- wọn gẹ́gẹ́bí i jíjẹ, mímu àti wíwọlé tọ aya ẹni ní àsìkò ọ̀ṣán..
wikipedia
yo
Ìyẹn ni pé kíkóra yo ó wá láti àsìkò ìdajì hàì (yíyọ́ àlùfãjárí) títí di ìrọ̀lẹ́ pátá (àsìkò wíwo òórùn)..
wikipedia
yo
Olóhùn (Allah) yòò wá a fi pípe ẹ̀sìn wọn àti ìgbàgbọ́ àti àmòjúkúrò níbí láìfi wọn jìrọ̀ ìkóradúró yìí fún wọn..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ sì ni pípè wọ́n yóò sì lẹ́kun gẹ́gẹ́bí nkan dáradára míràn yóò ti jẹ́ tiwọn nínú àwọn oore làǹtìlanti tí ó ti pa lẹ́sẹ sílẹ̀ fún eléyìí ní ilé ayé níháàyín àti ní ọ̀run.Ìrìnàjò sí ilé mímọ́ (Haji) ohun náà ní ìmúra gírí lọ sí ilé olóhùn (Allah) Olówó láti lọ jọ́sìn fún un ní àsìkò kan pàtó gẹ́gẹ́bí ó tíṣẹ́ wà nínú ìlànà Islam..
wikipedia
yo
Olóhùn (Allah) ti ṣéé ní òranyàn fún ẹni tí ô bá ní ìkápá bẹ̀ẹ̀ ní ìgbà ìṣẹ̀mí ní ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo..
wikipedia
yo
Nínú àsìkò hájì yìí ni gbogbo Mùsùlùmí jákèjádò ayé yóò kójọ sí ààyè tí ó lóore jùlọ lórí ilẹ̀, tí gbogbo wọn yóò máa ṣe ìjọsìn fún olóhùn kan ṣoṣo níbẹ̀ ,tí wọn yóò sì gbé ẹ̀wù kanwù – náà wọ̀..
wikipedia
yo
Kò ní í sí ìyàtọ̀ láàrin olórí ati ará ìlú, Olówó ayé ati mẹ̀kúnnù pẹlu funfun ati dúdú ninu wọn..
wikipedia
yo
gbogbo wọn yọ́ ọ má a ṣe àwọn ìṣe ìjọsìn mímọ́ kan tí ó ti ní àkọsílẹ̀..
wikipedia
yo
Èyí tí ó ṣe kókó jùlọ nínú rẹ̀ jẹ́ kíkáràdúró ní ààyè tí a mọ̀ sí arafá àti ríyínkẹ̀ ilé Olúwa (kàábá) Abiyì tí ó jẹ́ àdojúkọ gbogbo mùsùlùmí ní àsìkò ìjọsìn wọn pẹ̀lú ìlọsókè-lọ láàrín òkè Sáfà àti Moriwa..
wikipedia
yo
Níáàrì, kí ó ríi dájú wípé òun ṣe ohun kóhun ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà (Sunnah) òjíṣẹ́ e rẹ̀; bíb Muhammad (kí ikẹ̀ àti ọlá olóhun kí ó báa-Bákan-Bákan náà ni Islam tún fètò sí ìgbésí ayé àwọn eni tí ó gbà á lẹ́ṣin yálà ni ìwà wọn ní ẹyọ kọ̀ọ̀kan ni ó tàbí nígbàtí wọ́n bá wà níjọníjọ ni ọ̀nà tí oríire ayé àti tọrùn yọ ó fi jẹ́ tiwọn..
wikipedia
yo
Nítorí ìdí èyí ni ó fi ṣe fífẹ ìyàwó ní ètò fún àwọn àtẹ̀lé rẹ̀ tí ó sì ṣe wọ́n lójúkòkòrò lọ síbẹ̀..
wikipedia
yo
Ó sì ṣe ṣínà ṣíṣe àti ìwà panṣágà ní èèwọ̀ fún wọn àti àwọn ìṣesí-i-láabi míràn..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ ni ó sì ṣe dídá ibi pọ̀ àti Siṣàánú àwọn aláìní àti Talikà ní ọ̀ranyàn pẹ̀lú àmójútó wọn..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi o ti senilôjúkòkòrò lọ si ibi gbogbo iwa to dara ti o si se e ni òranyàn, bẹẹ gẹgẹ ti o si kininilo nipa gbogbo iwa burúkú ti o si ṣe e ni èèwọ̀..
wikipedia
yo
Síwájú síi, ó ṣe kíkó ọrọ̀ jọ lọ́nà mímọ́ gẹ́gẹ́bíi òwò ṣíṣe tàbí yíyàtá àti ohun tí ó fara pẹ́ eléyìí ní ẹ̀tọ́..
wikipedia
yo
Ní ìdàkejì ẹ̀wẹ̀, ó ṣe owó èlé (rìbá) àti gbogbo ọwọ́kọ́wọ́ àti ohun tí ó bá ti ní mọ̀dàrú àti awúrúju nínú ni èèwọ̀.Aláyẹ ìparí nípa ẹ̀sìn Islam ni ṣókí yàtọ̀ sí ohun tí a kà síwájú yìí, Islam ṣe àkíyèsí àìdọ́gba àwọn ènìyàn nínú dídúrótó sí ojú ọ̀nà ìlànà rẹ̀ àti sísọ ètò àwọn ènìyàn míràn..
wikipedia
yo
Nítorí-ìdí-èyi ni ó fi gbé àwọn ìjìyà amúnisá-kúrò-ẹsẹ̀-ẹsẹ̀ kalẹ̀ fún àwọn ìtayọ -ààlà tí ó bá wáyé nínú àwọn ìwo olóhun (Allah ) mímọ́; gẹ́gẹ́bíi kíkó (pípadà sínú kèfèrí lẹ́yìn ìgbà tí a ti gba Islam), ṣíṣe ṣìnà, mímu otí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ náà ni ó gbé àwọn ìjìyà adánílẹ̀ kalẹ̀ fún títasẹ̀ àgẹ̀rẹ̀ lórí àwọn ẹ̀tọ́ àwọn ènìyàn gẹ́gẹ́bíi pípààyàn, olè jíjà, píparọ́ àgbèrè mọ ẹlòmíràn, títayọ ààlà nípa lílù ẹlòmíràn tàbí sí ṣeé ní ṣùtá àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Ó ṣe pàtàkì láti fi rinlẹ̀ pé àwọn ìjìyà kọ̀ọ̀kan tí ó fi lélẹ̀ yìí ṣe wẹ́kú irunfin kọ̀ọ̀kan là í sí àṣejù tàbí àṣeẹ̀tọ́ níbẹ̀..
wikipedia
yo
Islam tún ṣètò, ó sì tún fi ala sí ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàrín àwọn ará ìlú àti àwọn adarí wọn..
wikipedia
yo
O sì ṣe títẹ̀lé àwọn adarí ní dandan fún àwọn ará ìlú nínú gbogbo ohun tí kò bá sì ṣíṣe olóhùn (Allah) nínú rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó sì ṣe yíyapa sí àṣẹ wọn àti àìgbọ́- àìgba fún wọn ní èèwọ̀ nítorí ohun tí ó lè tara èyí jáde nínú aápọn àti rúkèrúdò fún tẹrútọmọ.Ní àkótán , a le è fọwọ́gbàyà rẹ̀ pé Islam ti kákọjá mímọ àṣepọ̀ tí ó yanran-ún-tán àti iṣẹ́ tí ó yè kooro láàrín ẹrú olóhun (ẹ̀dá) àti “‘fọkàn rẹ̀ ní abala kan, àti láàrin ọmọ ẹ̀dá ènìyàn àti àwùjọ tí ó ń gbé níbẹ̀ nínú gbogbo Alaarí rẹ̀ ni abala míràn..
wikipedia
yo
Kò sí rere kan nínú àwọn ìwà àti àwọn ìbálò àyàfi kí ó jẹ́ pé ó ti ṣe ìfinimọ̀nà àwọn àtẹ̀lé rẹ̀ síbẹ̀ tí ó sì ṣe wọ́n lójúkòkòrò nípa dídúró tìí gbọin -gbọin..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ sì ni kọ́ aburú kan nínú àwọn ìwà àti àwọn ìbálò àyàfi kí ó jẹ́ pé ó tí kí wọn nílọ̀ gidigidi nípa àtimásúnmọ́ ọ tí ó sì kó ọ fún wọn..
wikipedia
yo
Èyí ni ó fi wá n hàn wá gédégbé pé ẹ̀sìn tí kò làbùkópa Kankan ní Islam jẹ́, ẹ̀sìn tí ó sì dára ní pẹ̀lú tí a bá gbé yiri wo ní gbogbo ọ̀nà.Ixàwọn Ìtọ́kasí lórí Internet Internet EBOIslam.com..
wikipedia
yo
Ìrìnkèrindò nínú Igbó Elégbèje ni orúkọ ìwé tí D.O..
wikipedia
yo
Fágúnwà kọ.Ìrìnkèrindò ni Ìwé Ìtàn-Àròsọ yìí dá lé lórí..
wikipedia
yo
Fágúnwà pe ní apá kẹta ògbójú ọdẹ́ nínú Igbó Irúnmọ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Ìyàlẹ́nu l'ó jẹ́ fún mi pé bí ó tilẹ̀ ti jẹ́ pé nkò sọ fún púpọ̀ ninú àwọn ọ̀rẹ́ mi nípa ọkùnrin na tó wọnni, síbẹ̀ ogunlọ́gọ̀ àwọn ènìà l'ó ti gbọ́ nípa ọkùnrin nã, kí ó sì tó di pé a jẹun arọ tán lọ́jọ́ ná àwọn ènìà ti rọ́ dé ilé wa..
wikipedia
yo
Àyá mi jà púpọ̀ nítorí igbe yí nítorí mo nbẹ̀rù kí ó má bã jẹ́ iwin burúkú tí òkìkí rẹ̀ ti kàn jákèjádò òde aiyé tí a npè ní Ẹlẹ́gbára..
wikipedia
yo
Iwin burúkú ni, bí ó bá nbọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ tí a npè ni ọmọ Ẹlẹ́gbára ni ó ma nṣaju ti nown ma nkéde bíbọ̀ rẹ̀ fún gbogbo ohun alàyè..
wikipedia
yo
Nigbati a rin si iwájú diẹ, a bẹrẹ wọ ilu na ni ọ̀kánkán sugbọn ọna ti a ntọ́ lọ tubo didi kekere si i afi bi eni pe enia ko ngbe ilu na ni, nigbati o sa pe ṣa, a yọ si ilu Yi.... G'ori oye Snná gbe Òmùgọ̀diméjì lọ oju-iwe 49-54ibití alejo mi soro na fun mi mọ lọjọ ti a tun nkọwe na ni eyi, a ba da owo duro lọjọ na, a ki awon ti o wa gbo ọrọ w àpé ki Nown ma lọ silẹ ki nwọn tun pada lọjọ keji..
wikipedia
yo
…Ẹbọra ìgbéraga-ìbànújẹ́ àti Ahọ́ndiwúrà ìyàwó rẹ̀ ojú-ìwé 55-59"A kúrò ní ìlú àwọn Èdìdàrẹ́ lẹ́hìn tí a ti gbé etí ibẹ̀ fún odidi oṣù mẹ́ta gbáko, a kọ orí sí ọ̀nà wa..
wikipedia
yo
Ẹ má jẹ́kí èyí yà yín lẹ́nu pé a pẹ́ tóbẹ̃ ní ìlú kan tí a kó lọ sí ibití nwọ́n rán wa..
wikipedia
yo
Ọba pãpã ti fún wa ní àṣẹ bẹ̃ kí a tó kúrò ní ilé, ó ti wí fún w àpé bí a bá dé ibikíbi tí a rí i pé ohun tí a nfẹ́ ṣe yíò gbà ni tó oṣù mẹ́fà tàbí jù bẹ̀ lọ kí a máṣe kánjú, kí a ṣe é Dada....A fi ojú wa rí ọ̀run àpãdì ojú-ìwé 60-70"Bí a ti dé ibìkan tí ó dákẹ́ minimini báyĩ, tí igbó ibẹ̀ di tí ó dúdú mirinmirin ni a rí iwin kan tí ó nbọ̀, ó dàbí ọba gan, ìgbàtí a sì kọ́ rí i, a ké ‘Kábíyèsí', a ti gbàgbé pé aginjù baba-lòrìṣà ni wá, bẹ̃ni kò sí ibití ẹbọra nã fi yàtọ̀ sí ọba..
wikipedia
yo
Fìlà orí rẹ̀ dàbí adé, bàtà ẹsẹ̀ rẹ̀ dàbí bàtà ẹsẹ̀ àwọn alágbára, bẹ̃ni ẹ̀wù ọrùn rẹ̀ kò yàtọ̀ sí ti ọba tí ó ti gba adé láti ọwọ́ Odùduwà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn iwin míràn ni ó tẹ̀lé e, ọ̀kan nínú àwọn iwin nã sì gbé àpótí kan lé orí, ó nrí u tẹ̀lé e..
wikipedia
yo
Ìgbátí gbogbo àwa òde dọ̀bálẹ̀ tí a kí iwin pàtàkì yí, ó dáhùn ó ní,Wèrédìran ti ńgbé ilé Òmùgọ́parapọ̀ ojú-ìwé 71-75-75”A kọjú sí ọ̀nà wa, à nlọ, a kò sì rí nkankan jù bẹ̀ lọ títí ó fi di òwúrọ̀ ọjọ́ kan bayi, ní nkan bí agogo mẹwa, tí a rí ọ̀nà kan tí ó yà bàá pa ọ̀tún lọ..
wikipedia
yo
…Ìgbéyàwó Ìrìnkèrindò pẹ̀lú àbúrò olókun iwin inú omi ojú-ìwé 76-100"ṣùgbọ́n kiní kan kò ní ṣàì yà yín lẹ́nu nípa èmi Papa ẹ kò bí mi nkan nã dán? On ni wípé láti ìgbàtí a ti kúrò ní ibití Ẹlẹ́gbára ti le wá, ọkàn mi kò kúrò lára obìnrin tí ó ṣe ìtọ́jú mi nígbàtí Ẹlẹ́gbára fi lé mi kọjá òkè odò..
wikipedia
yo
Gẹgẹ bi mo ti sọ ṣaju, nkò fẹ́ràn obinrin ṣaju akọkọ na, nwọn tilẹ̀ nmá sì mí ni, nkò sì mọ́ ohun ti o fa ti fífẹ tí mo dédé wá fẹ́ràn obìnrin nã ju ti itọju mi ti o ṣe nígbànã lọ, ṣugbọn ki a ma sa fá a gun lọ titi, gọngọ ori emi mi ni ọmọ na duro lé, ọ̀rọ̀ rẹ ki Isi í lẹ́nu mibẹ tóbẹ̃ ti ó jẹ́ pé àwọn ẹnìkejì mi ma nfi mi ṣe yẹ̀yẹ̀ sá ní karun-enia oju-enia oju-iwe nkan-ọrọ nkan ni a fi oju ri nigbati a kuro ni ilu yi tan ko si ayé nisisiyi lati sọ gbogbo wọn..
wikipedia
yo
Sibẹsibẹ na, nkò gbọdọ̀ sai sọ nkan ti ó ṣẹlẹ̀ si mi ni ilú ti a ńpè ni ìtànjẹ-enia..
wikipedia
yo
“Kò si eniti o wa ni ode aiye yi ti ko ni àgbélébù tiree àgbélébù ki Isi ìtilẹ̀ fi ibi nkan rere silẹ..
wikipedia
yo
Mo ni àgbélébù kan ninu irinajo yi, àgbélébù na si ni igba Kemi mi, aiyedin-ẹda..
wikipedia
yo
Mo rò pé ẹ ó rántí irú ọ̀rọ̀ burúkú tí ó sọ níwájú Òmùgọ́diméjì ọba ìlú àwọn Èdìdàrẹ́, ẹ ó sì ṣàkíyèsí pé ọ̀rọ̀ rẹ kò ju àti fi wá ojú Òmùgọ̀diméjì mọ́ra lọ..
wikipedia
yo
...Ogun ibodè Igbo Elégbèje ojú-ìwé 109-117"bayi ni ọkunrin na wí, mo sì ńfẹ́ bá a sọ̀rọ̀ kí ntúbọ̀ wádĩ nípa nkan tí ó sọ, ṣùgbọ́n, wéré l'ó kọjá, kò dúró mọ́..
wikipedia
yo
Nkan tí a kò ṣe àkíyèsí ni ọ̀wọ̀n nlá kan tí ó bá ojú ọ̀run lọ, tí ó dúró ní ẹnu ọ̀nà igbó nã..
wikipedia
yo
Ìgbátí ò bá ṣe tí a bá wo òkè ọ̀wọ̀n yí, a dàbí ojú ènìà..
wikipedia
yo
tí ó bat ún ṣe, a dàbí ojú kìnìún, ìgbátí ó tún ṣe, a dàbí ojú ẹkùn..
wikipedia
yo
Bí o bá sit ùn yí padà a dàbí orí ejò nlá, a ma yọ ahọ́n jáde bérébéré lẹ́nu....d.O..
wikipedia
yo
Nelson Publishers Ltd in Association With Evans Brothers (Nigeria Publishers) Ltd; Ibadan, Nigeria..
wikipedia
yo
Ògbójú ọdẹ ninu Igbo Irúnmọ́lẹ̀ jẹ iwe itan-aroso ti omowe D.O..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ìwé ìtàn-àròsọ tí a kọ́kọ́ kọ ní èdè Yorùbá, tí ó sì jẹ́ ọ̀kan lára ìwé ìtàn tí a má a kọ́kọ́ kọ ní èdè Áfíríkà ..
wikipedia
yo
Ó sọ̀rọ̀ nípa ìgbòkègbodò ògbójú ọdẹ kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ àkàràogun, àti ohun tí ojú rẹ̀ rí lóríṣiríṣi nínú ìrìn-àjò rẹ̀ nínú igbó..
wikipedia
yo
Àwọn nkan bí idán, iwin, ẹbọra àti àwọn òòṣà oríṣiríṣi ṣe fìtínà rẹ̀ nínú igbó tí òǹkọ̀wé pè ní Igbó Irúnmọ́lẹ̀..
wikipedia
yo
O jẹ iwe itan-aroso bèla ti a ka ni ede Yoruba..
wikipedia
yo
Ìwé ìtàn àròsọ tí ó tẹ̀lé ìwé yí láti ọwọ́ònkòwé kan náà ní Igbó Olódùmarè..
wikipedia
yo
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wole Soyinka se ògbufọ̀ iwe itan aroso Ògbójú ọdẹ ninu Igbo Olodumare si ede Gẹẹsi..
wikipedia
yo
Like Igbo Olodumare, it was yálà for the Stage, in both English and Yoruba.Àwọn ìtọ́kasí1938 novelsworks based on folklore1938 debut novelsYoruba-language literaturenovels by Daniel o..
wikipedia
yo
Fágúnwà kọ́.Eléyìí jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn Ìwé Ìtàn Àròsọ ti D.O..
wikipedia
yo
Ó sọ ìtàn Olówó-ayé àti ìrìnàjò rẹ̀ ní Igbó Olódùmarè..
wikipedia
yo
Ó sọ bí ó ṣe dé ọ̀dọ̀ Baba-onírùngbọ̀n yẹnke àti bí ó ṣe rí òpin Òjòlá-ìbínúd.o..
wikipedia
yo
Nelson publisher Ltd in Association with Evans Brothers (Nigeria) Publishers Ltd; Ibadan, Nigeria..
wikipedia
yo
Eriooki Adeagboadeagboo Wo Aagbo FAtókí (1991) EHẹ́lámánì..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ àkọ́sọohun tó gbé mi dé ìdí à ń kọ ìwé yìí ní ìgbàgbọ́ àti ìhà tí àwọn ènìyàn kọ sí àwọn ọmọ tí a ń pè ní Eláàárín..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ rí àwọn ọmọ wọ̀nyìí gẹ́gẹ́ bí àbíkú, ẹlẹ́gbẹ́, ogbanje, ọmọ ìyanu, àbáféférin-ọmọ ẹlẹ́mìí-ọmọ-ọmọ àti à-ọmọ..
wikipedia
yo
Àwọn orúkọ wọ̀nyìí fi hàn pé ìṣòro ńlá wa láti dá Ebàáte mọ̀..
wikipedia
yo
lọ́wọ̀ọ́ ìgbà tó sì jẹ́ pé a kò lè fi ogun ré gbárí pé Esco nìyìí, mo wá lọ sí àròjinlẹ̀ ọkàn, mo pe kọ́lọ́fín ọ̀pọ̀lọ́ jáde, mo wá rí i pé aṣekúpani jẹ́ àjíǹde-òkú tó ń pọ́n ọbẹ̀ sùn, tó tún ypò rọri..
wikipedia
yo
Ẹ̀mí àìrí tó sì ń bá wọn lò jẹ́ èyí tó ṣòro láti ṣàpèjúwe..
wikipedia
yo
A ní àdánwò-ọmọ ni wọ́n, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì dúró fún tibi-tirẹ̀ tó bá bá àwọn lọ́kọláya tó bá lùgbàdì wọn.Ní ti agbára, wọ́n ní agbára jù ajé àti oṣó lọ..
wikipedia
yo
Ẹyin ìyá mi, apani-má-Háà-ogun, ìbá! Pẹ̀lú fàájì ní Eláàárín ṣe ń wọ inú obìnrin-kó..
wikipedia
yo
Taa ni yòò yẹ̀ ẹ́ lọwọ rẹ̀ wò? Wọ́n ní agbára láti yí padà tàbí taari ọmọ inú aboyún jáde nígbà tí wọ́n bá fẹ́ lo ààyè ibẹ̀..
wikipedia
yo
Bahrain tabi ile-ọba Bahrainni ọdun 1995, àwọn eniyan ti o n gbe orile-ede yii to ẹgbẹrun lọ́nà ẹẹdẹgbẹta ati ààbọ̀ (555,000)..
wikipedia
yo
Àwọn èdè náà ní ed (Farsi) ti àwọn tí ó ń sọ ọ́ ẹgbẹ̀rún méjìdínláàádọ́ta (48, 000); UU (Urdu) tí àwọn tí ó ń sọ ó tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún (20,000) àti àwọn èdè Filipiìní (phillilli) mìíràn tí àwọn tí ó ń ṣọ́ wọn tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún (20,000)..
wikipedia
yo
Èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbayì ní ilẹ̀ yìí sí i gẹ́gẹ́ bí èdè ọ̀wọ̀ àti èdè iṣẹ́ àbẹ̀wò sí ìlú (Tourism). Àwọn orílẹ̀-èdè Asia..
wikipedia
yo
Àwọn Bahama ránka tàbí Loníbiṣẹ́ bí orílẹ̀-èdè àjọní ilẹ̀ àwọn Bahama, jẹ́ orílẹ̀-èdè elédè tó ní àwọn erékùṣù 29, 661 cays, àti 2,387 erékùṣù kékeré 2,387 (apata).. G)..
wikipedia
yo
O bùdó sí inú Okun Atlantiki ní àríwá Kuba ati Hispaniola (Dominiki olominira ati Haiti), àríwáiwoorun awọn Erékùṣù Turks ati Caingcos, ati Guusuila Orilẹ-ede awọn ipinlẹ fọ́nka ilẹ Amẹrika (nitosi ipinlẹ Florida)..
wikipedia
yo
Bí Jeografi, àwọn Bahama wa ní asopọ Erékùṣù kanna bi Kuba, Hispaniola (Dominiki Olómìnira ati Haiti) ati awọn Erékùṣù Turks ati Caicos..
wikipedia
yo
Àwọn onílá ibè tẹ́lẹ̀ ni àwọn ẹ̀fọ́ ti arawaka, àwọn Bahama ní ibi tí ogún tí gunle sí ní ilé ayé tuntun ní 1492..
wikipedia
yo
Bótilẹ̀jẹ́pé àwọn ará Speìnmu kò ṣe amúnisìn àwọn Bahama, wọ́n kọ àwọn Lucaya àbínibí ibẹ̀ (èyí ni orúkọ tí àwọn Δ Bahama unpé ara wọn) lọ sí oko ẹrú ní Hispaniola..
wikipedia
yo
Láti 1513 dé 1650 ẹnìkankan kò gbé orí àwọn erékùṣù yí, kó tó di pé àwọn olùmúnisin ará Britani láti Bermuda tẹ̀dó sí erékùṣù eleuthera.ìtọ́ka..
wikipedia
yo
batinilinlinẹsẹ̀ ẹgbẹ ẹbi ede Austronenesian ni ede yii..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń ṣọ́ ọ fẹ́rẹ̀ẹ́ tó mílíọ̀nù mẹrin (3.8 million) ní erékùṣù Baali (Bálì) ni In-indoniì (INDONESIA)..
wikipedia
yo
Àkọtọ́ Bálìísì àti ti Roma (Blinese and Roman Alphabet)ni wọ́n fi ń kọ èdè yìí sílẹ̀...
wikipedia
yo
Pupọ ninu àwọn tí ó ń ṣọ́ ọ yìí ni ó wà ní odiBetiani (Pakistan) ní BaSisiani (Bluchist)..
wikipedia
yo
BaluClí yii ni Ipinle (Province) ti o wa ni apa iwọ-oorun juni rkcusus..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń sọ èdè yìí ní Bluchist To mílíọ́nù (ìran), Konbactàánú (Ibadan) àti In-India (India)..
wikipedia
yo
Tí kan wà tí wọ́n ń pè ní Bamichi Academy tí ó ń n sí pé Àkọsílẹ̀ èdè yìí payé.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ède..
wikipedia
yo
Btálákà tàbí Blosibachi or BARTACH Egbe ÈDÈ TÍ A Ń PÈ NI iraSarahẹ́múlà NI BÍ JÉSÙ..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń sọ èdè yìí ní Bluchius To Muòyeẹ (ìran), Inbganib (Ibadan) àti In-India (India)..
wikipedia
yo
Tí kan wà tí wọ́n ń pè ní Bkòchi Academy tí ó ń n sí pé Àkọsílẹ̀ èdè yìí Ppa.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àwọn èdè Balto-Slavicẹgbẹ́ àwọn èdè tí wọ́n ní Baltic àti Slavic ni àwọn wọ̀nyí tí wọ́n wá ń pe àwọn méjèèjì papọ̀ ní Baltó-Slavic..
wikipedia
yo
Ọmọ ẹgbẹ́ ni àwọn èdè wọ̀nyí jẹ́ fún àwọn ẹ̀yà èdè (branch) tí à n pè ní Indo-European (in-do-do-pi)..)..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń sọ balù-tó-ààfinìkì yìí ti mílíọ̀nù lọ́nà ọọdunrun eniyan (300 million people)..
wikipedia
yo
Eléyìí tí ó ju ìlàjì lọ nínú àwọn ènìyàn wọ̀nyí ni ó ń sọ èdè Rọ́síà (Russian) èdè àìyedè díẹ̀ wà lórí pé biya ibì kan náà ni gbogbo àwọn èdè yìí ti ṣe tàbí pé nítorí pé wọ́n jọ wà pọ̀ tí wọ́n sì jọ ń ṣe pọ̀ ló jẹ́ kí ìjọra wà láàrín wọn.Ìtọ́kasí wọn..
wikipedia
yo
tíṣàmẹsẹ̀:Iṣiara ẹgbẹ́ ti ìlà-oòrùn àwọn èdè Indo-Aryan (in-dò-Aryan languages ni ẹ̀sìnÒfin..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń ṣọ́ ọ tó mílíọ̀nù mẹrinla àbọ̀ (14.5 million)..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń sọ èdè assamẹsẹ̀ yìí tún wà ní huhu àti Bangladesh..
wikipedia
yo
Èdè Armenia jẹ́ ọ̀kan lára èdè Indo-European (in-u-rọ́pò) kan ní eléyìí..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń ṣọ́ ọ ní orílẹ̀-èdè Armenia jẹ́ mílíọ̀nù mẹta ati ẹgbẹrun mẹfa (3.6 million)..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó lọ ṣe àtìpó ní Europe (Úróòpù), Amẹ́ríkà (USA) àti àárín gbùngbùn Ìlà-Oòrùn Àgbáyé (Middle East) náà ń sọ èdè náà..
wikipedia
yo
Èdè Armenia àtijọ́ (Classical Armenian tí wọ́n ń pè ní GraBar ni wọ́n kọ́kọ́ fi kọ Lítíréṣọ̀ sílẹ̀ ní gbogbo àgbáyé..
wikipedia
yo
Wọ́n kọ ó ní nǹkan bíi sétúrì karùn-ún lẹ́yìn ikú Jésù Kírísítì èdè graBar yìí ni wọ́n ń lò gẹ́gẹ́ bí èdè ẹ̀sìn fún àwọn ìjọ ilẹ̀ Armenia òde òní, lẹ́tà álúfábẹ́ẹ̀tì méjìdínlógójì ni wọ́n fi ń kọ èdè yìí sílẹ̀..
wikipedia
yo