cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àwọn tí ó ń ṣọ́ Abkhaz tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́rùn-ún ènìyàn ní ìpínlẹ̀ tí a ń pè ní Abkhaz ní Georgia..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ń sọ èdè yìí ní apá kan ilẹ̀ Tọ́kì (Turkey)..
wikipedia
yo
Atọrẹ Cyrillic (Sirilọ́hùn) ni wọ́n fi ń kọ èdè yìí sílẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn èdè..
wikipedia
yo
(i) ‘FA’ the cloth absor all the water in the Bowl; aṣọ náà fa gbogbo omi inú abọ́ náà (ii) ‘Mo' I have not absorking all their Rules; n kò tíì mọ gbogbo òfin wọn..
wikipedia
yo
‘Po’ maize was kun last year; àgbàdo po ní ọdún tí ó kọjá)..
wikipedia
yo
(i) ‘Da’ the sacrifice has been accepted; ẹbọ naa ti da (ii) ‘fin' the sacrifice would be accepted by the deities; ẹbọ naa yóo fin (iii) ‘gbo’ he Símónì what I say; ó gbo ọ̀rọ̀ mi (iv) ‘Gba’ he accepted the money; ó gba owó náà (v) ’yan' the kóts have been accepted by the deity; obì naa ti yan..
wikipedia
yo
‘Gba’ our house can accommodate four people; ilẹ̀ wá lè gba eniyan mẹrin..
wikipedia
yo
(i) 'sin' he accompanied him there; o sin in lọ si ibẹ̀ (ii) ‘Ba' He accompanied Olù to the doctor; O ba olu lọ sọdọ Dokita..
wikipedia
yo
'Gba' he achieved High marks in the Examination; ó gba máàkì tó ga nínú ìdánwò..
wikipedia
yo
‘Gba’ do you acknowledge that you are wrong?; se ó gbà pé ó jẹ̀bi?
wikipedia
yo
‘Rọ’ he added three to four to make seven; ó ro ẹẹ́ta mọ́ àpọ́sítélì láti di eéje...
wikipedia
yo
(i) ‘PA' The Rain was beating him; Ojo n pa a (ii) ‘Gbo’ he beats a red-hot cutlass with a Hammer so as to respe it; O gbọn ada.(III) 'Bo' he beats the earth-floor; O bọlẹ̀..
wikipedia
yo
(v) ‘Po' she beats eggs in milk; ó po ẹyin ninu mílíìkì (vi) 'na' we beat them in football; a na wọn nínú eré bọ́ọ̀lù..
wikipedia
yo
(i) ‘Mo’ to work hard does not mean that the worker will be rich; gidigidi kò mọ́là..
wikipedia
yo
Ẹbọ a fin; the sacrifice would be accepted by the deities, e.G..
wikipedia
yo
asínàsíàChinese (àsìsì èdè Àwọn Malac (Málà kan) Kan ní eléyìí tí ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ fún àwọn èdè tí wọ́n ń pè ní Auohùn (Èdè tí wọ́n ń sọ ní ilẹ̀ Australia, New Zealand àti Ásíà)..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn bu miliọnu mẹ́ta ni ó ń sọ èdè aṣinisí ní apá kan ilẹ̀ Sumatra àti INDONESIA..
wikipedia
yo
Wọ́n tún máa ń pe èdè yìí ní AChehn àti ATHhnhn..
wikipedia
yo
Afghanistan ní bodè mọ́ Pakistan ní ilà-ọ̀run àti ní gúúsù; mo ìran ní ìwọ̀-ọ̀run; mo Turkmenistan, Uzbekistan, àti Tajikistan ní àríwá; àti mọ́ Ṣáínà ní àríwá-ìlà-ọ̀run..
wikipedia
yo
Gbogbo ilẹ̀ ibẹ̀ fẹ̀ tó , orílẹ̀-èdè olókè ní tó ní ilẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ní apá àríwá àti gúúsù-ìlà..
wikipedia
yo
iye aráàlú ibẹ̀ fẹ́ ẹ pọ̀ tó 32 mílíọ̀nù, tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà àwọn Pashtún, tajík, Hazara ati Uzbek.Ninu ètò ìkànìyàn 1995, àwọn eniyan tí wọ́n sọ pé ó wà ní ìlú yìí lé díẹ̀ ní mílíọ̀nù mọkanlelogun (21,017.000)..
wikipedia
yo
Èdè tí wọ́n ń sọ ní ìlú yìí tó àádọ́ta ṣùgbọ́n ìlàjì nínú àwọn tí ó wà ní ìlú náà ni ó ń ṣọ́ pásítọ̀ (PASHto) tí òun àti darí jọ jẹ́ èdè ìjọba (Official language).Darí (Darí) yìí ni orúkọ tí wọ́n ń pè Persian (Pásíà) ní Bráànbha..
wikipedia
yo
Darí yìí ṣe pàtàkì gan-an ni gẹ́gẹ́ bí èdè tí ìjọba ń lò (lingua Franca)..
wikipedia
yo
Fun ti owo ti o jẹ mọ́ gbogbo agbaye, ede Gẹẹsi ti n gbilẹ si i..
wikipedia
yo
Àwọn èdè Mikùń tí wọ́n ń sọ ní ìlú yìí ní TadG, Uzbek, Tümen, Baluchi, BraChic àti Pashatọ́kasí..
wikipedia
yo
Apẹja Ave dúró fún African-American Udcular English, ìyẹn ni, èdè Gẹ̀ẹ́sì tí àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà ń sọ ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Àwọn orúkọ mìíràn tí wọ́n tún ń pe èdè yìí ní Black English Udcular (Bev), Afro-American English àti Black English..
wikipedia
yo
Àwọn àmì ìdámọ̀ èdè yìí ni pé wọn kì í lọ ‘s’ tí ó jẹ́ atọ́ka ẹnì kẹta ẹyọ, bí àpẹẹrẹ, she walk , wọn kìí lọ bẹ, bí àpẹẹrẹ, they real fine..
wikipedia
yo
Wọ́n sì máa ń lọ bẹ̀ láti tọ́ka ibà atẹ́rẹrẹ bárakú, bí àpẹẹrẹ, sometime they be Walking round here..
wikipedia
yo
Àwọn kan sọ pé láti ara kirio (Creole) ni ṣùgbọ́n àbùdá rẹ̀ kọ̀ọ̀kan tí a ń ṣe àkíyèsí rẹ̀ lára èdè Gẹ̀ẹ́sì tí wọ́n ń sọ ní Gúsù Amẹ́ríkà jẹ́ kí àwọn kan gbà pé láti ara èdè Gẹ̀ẹ́sì ni ó ti wáyé..
wikipedia
yo
Èdè yìí wà ní àbùdá tirẹ̀ nígbà tí àwọn dúdú kọjá sí àwọn ìlú ńláńlá..
wikipedia
yo
Wọ́n wá ń lo èdè yìí gẹ́gẹ́ bí àmì àdámọ̀ fún ara wọn.Ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Èdè Ìwọ̀ Oòrùn Jámínì (a West Germany language) ti ó waye lati ara Dọrọ (dutuh) ni eléyìí tí wọn n sọ ni gusu Afirika..
wikipedia
yo
Wọ́n ń ṣọ́ ọ ní Nàmíbíà, Màláwì, Zambia àti Zimbabwe..
wikipedia
yo
Àwọn kan tí ó sì ti ṣe àtìpó lọ sí ilẹ̀ Australia àti Canada náà ń sọ èdè náà..
wikipedia
yo
Wọ́n tún máa ń pa èdè yìí ní keepú DÒò (lápá Dutch)..
wikipedia
yo
Èdè àwọn tí ó wá tẹ ilẹ̀ Gúsù Afírika dó ní Ṣétúrì kẹtàdínlógún (17th Century) ni ṣùgbọ́n ó ti wá yàtọ̀ sí èdè Doodji (Dutch) ti ilẹ̀ Úróòpù (Europe) báyìí nítorí èdè àdúgbò kọ̀ọ̀kan ti ń wọ inú rẹ̀..
wikipedia
yo
Èdè yìí ni èdè tí ó lé ní ìdajì àwọn funfun tí ó dó sí gúsù Arikarika ń so..
wikipedia
yo
Ìdá Àádọ́sàán n-an àwọn tí obí wọn jẹ́ ẹ̀yà méjì ni ó sì ń sọ èdè yìí pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Láti ọdún 1925 ni wọ́n ti ń lo èdè yìí pẹ̀lú èdè Gẹ̀ẹ́sì gẹ́gẹ́ bí èdè ìjọba..
wikipedia
yo
Èdè ainú èdè kan tí ó dá dúró ní òun nìkan ni èdè yìí..
wikipedia
yo
A kò mọ́ iye ẹni tí ó n sọ ọ́ ṣùgbọ́n ètò ìnìyàn ọdún 1996 sọ pé marundinlogun ni wọ́n..
wikipedia
yo
Ni ibẹrẹ sétúrì ogun, pupọ núnú awọn ohun ti o ṣe pataki ninu ede ati asa ainu ni jepanisi ti gba ipo wọ́nÀwọn ede..
wikipedia
yo
Aanuanu, àkànkọ́ ènìyàn bíi Milionu méje ni ó n sọ èdè yìí ní pàtàkì ní orílẹ̀-èdè Ghana..
wikipedia
yo
A máa ń lọ Akan fún àwọn èdè tí ó fara pera wọ̀nyí aṣhante, fante àti iwì ti àwọn tó ń sọ̀ wọ́n gbọ́ ara wọn ní àgbọ́yé dààyè kan ṣùgbọ́n tí wọ́n kà sí èdè ọ̀tọ̀ọlọ nítorí àṣà àti ọ̀nà ìgbà kọ nǹkan sílẹ̀ wọ́n tí kò bára mu..
wikipedia
yo
Èdè ìṣèjọba àkọtọ́ Romaãnú ni wọ́n lò láti kọ ọ́ sílẹ̀.Àwọn ẹ̀yà àbínibí ní Ghana..
wikipedia
yo
Taaasepuánèdè ṣẹ̀mílóró kan ni eléyìí tí wọn ń sọ ní ilẹ̀ Mesotátá láàárín Senturu 2300 sí 500 ṣáájú ibi Kírísítì © To C500)..
wikipedia
yo
A mú orúkọ tí ó gbẹ̀yìn yìí láti ara àwọn ẹ̀ka-èdè rẹ̀ méjèèjì (Assyrian àti Babylonian)..
wikipedia
yo
Èdè yìí ni ó rọ́pò Sumerian tí wọ́n ti n sọ ní ìpínlẹ̀ yìí tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Ẹ̀ka-èdè Babylonian ni wọ́n ti ń lò gẹ́gẹ́ bí èdè ìfiàtàn (lingua] France) láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ láti nǹkan bíi Ejibitiọ̀nù kìíní ṣáájú ibi Kírísítì (1st Millennium B.C) ṣùgbọ́n láàárín sétúrì díẹ̀ èdè Aramaic ti gba ipo rẹ̀ síbẹ̀ Babylonian sí ti jẹ́ èdè tí wọ́n ń lò fún ìwé kíkọ àti kíkà ti di Ejibitiónu kìíní lẹ́yìn ikú Kírísítì (1st Milleni A.D)..D)..
wikipedia
yo
Ìwà Kunimin (Cuineform Script) ni won fi kọ Akan sílẹ̀..
wikipedia
yo
Sétúrì kọkàndínlógún (19th Century) ni wọ́n tú u palẹ̀ (deciòòlù) sí èdè tó yẹ tawo-tó.”
wikipedia
yo
Ó ní bodè mọ́ Montenegro ní àríwáìlàòrùn, Kosovo ní ríwàilaọrun, orílẹ̀òmìnira ilẹ̀ Makedonia ní ìlàọrun àti Girisi ní gúsù àti gúsùìlàòrùn..
wikipedia
yo
O ni Eti-Omi ni ẹgbẹ Omi-okun Adulamuatiki ni iwoorun, ati lẹgbẹ omi-okun Ionia ni Ámùilarun..
wikipedia
yo
Ó fi iye tó dín ní jìnnà sí Italy, níkọjá Strait of Otranto to ja Adriatic Sea pọ̀ mọ́ Ionian Sea.Albania jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ un, náto, àgbájọ fún abo àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ní Europe, Ìgbìmọ̀ Ilẹ̀ Europe, Àgbájọ ọwọ́ Àgbáyé, Àgbájọ ìpàdé onímàle bẹ́ síni ọmọ ẹgbẹ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ ìṣọ̀kan fún Meditẹrantéun..
wikipedia
yo
Albania ti fẹ́ di ọmọ ẹgbẹ́ ìsọ̀kan Europe láti January 2003, bẹ́ síni ó ti tọrọ láti di ọmọ ẹgbẹ́ láti 28 April 2009.Albania jẹ́ òṣèlú Onílé Onílé pẹ̀lú Ikọ́wọ̀ọ́ ìwọ yipada..
wikipedia
yo
Ìlúìlú Albania, kònà, jẹ́ ilé fún àwọn eniyan bí 600,000 ninu àwọn eniyan 3,000,000 tó wà lórílẹ̀-èdè ná..
wikipedia
yo
Adéwá ọjà Alòlòrí ti sí orílẹ̀-èdè sílẹ̀ fún ìyanjù Ìrísókè, Àgàgà fún fún Ìsokè àti ètò Àdárírí irinna.
wikipedia
yo
Ile re ni ti orile-ede ti o tobijulo ni Okun Medimentaṣèrànwọ́, ekeji tótóbijùlọ ni orile Afrika leyin Sudan, ati ikokanla tótóbi lagbaye.Algeria I Bode ni àríwáila mó pelu Tunisia, ni ilaorun pelu Libya, ni iwoorun pelu Mòrókò, ni guusuiwoorun pelu apaiwoorun Sahara, Mauritania, ati Mali, ni guusuila pelu Niger, ati ni ariwa pelu Okun Medikọ̀wé Seaun..
wikipedia
yo
Títóbi rẹ̀ fẹ́ jẹ́ , bẹ̀ sì ni iye àwọn ènìyàn rẹ̀ jẹ́ 35,700,000 ní January 2010..
wikipedia
yo
The capital of Algeria is Algiers.Algeria jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Ìparapọ̀ Àwọn orílè̩‐èdè, ÌṢỌ̀KAN Afrika, àti OPEC..
wikipedia
yo
Bakanna o tun kopa ninu dida ikoẹnu owo isokan MaGHreb.itọkasiji..
wikipedia
yo
Àwọn èdè Altaicàkójọpọ̀ èdè tí ó tó tó ọgọ́ta tí nǹkan bíi mílíọ̀nù-dínlọ́gọ́fà ènìyàn ènìyàn ń sọ ni à ń pè ní ‘ìdáAltai
wikipedia
yo
Wọ́n ń sọ àwọn èdè wọ̀nyí ní penisúlà Balkan (Balkan penisúlà) ní ìlà-oòrùn àríwá ilẹ̀ àsíá..
wikipedia
yo
Wọ́n pín àwọn èdè wọ̀nyí sí ẹgbẹ́ Turkic, Mongolian àti Manẹgbẹ̀rún-túngus..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ lórí ìbẹ̀rẹ̀ ìsókè àwọn èdè yìí kò pọ̀..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ lórí Turkic wà ní nǹkan bíi sétúrì kẹjọ (American century) ṣùgbọ́n a kò mọ nǹkan kan nípa Mongolian ṣáájú sétúrì kẹtala (13th century)..
wikipedia
yo
O to sintúrì Kẹtani (17th Century) kí a tó rí Àkọsílẹ̀ kànkà nípa Manchu..
wikipedia
yo
Ní sétúrì ogún (20th Century), ìgbìyànjú tó ga wáyé láti sọ àwọn èdè yìí di èdè ode oni..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ ìwé tí ó wuyì ni ó ń jáde tí a fi àwọn èdè àdúgbò kọ, bí àpẹẹrẹ, uzbek..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ṣe àtúnṣe sí àwọn Àkọsílẹ̀ tí ó ti wà tẹ́lẹ̀, bí àpẹẹrẹ ọlọ́gbọ́nshitọ́kasíàwọn ède..
wikipedia
yo
Ètò ìkànìyàn 1995 sọ pé àwọn eniyan ibẹ̀ jẹ́ ẹgbẹrun lọ́nà òjòjí ó lé mẹta (43, 000)..
wikipedia
yo
Ìdá àádọ́rùn-ún nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tí ó ń gbé ibẹ̀ ni ó ń ṣọ́ Samoan..
wikipedia
yo
Orúkọ Yorùbá jẹ́ ohun pàtàkì tí àwọn Yorùbá ń lò jákè-jádò gbogbo ibi tí wọ́n ti ń sọ èdè Yorùbá bí Ìbìní, Togo àti Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Nipasẹ iṣẹ́ awon baba nla baba awon Yoruba, won n fun omo won lorukọ nibi ayẹyẹ ti o maa n waye ni ojo Kẹẹ̀jọ leyin ibimọ..
wikipedia
yo
Àwọn orúkọ àwọn ọmọ jẹ́ àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ nípa ifá dídá tí ọ̀pọ̀ babaláwo bá dá, ṣùgbọ́n ni ayé òde-òní, orúkọ ọmọ tún le wá láti ọ̀dọ̀ àwọn tí ó bá ní ipò tọ̀gá nínú ẹbí pẹ̀lú baba, ìyá, obì àwọn òbí méjèèjì tàbí ẹni tí ó súnmọ́ wọn gbágbá..
wikipedia
yo
Ìyá àti bàbá, àti alásún-un-mọ́ wọn lè fún ọmọ tàbí àwọn ọmọ ní orúkọ tọba wù wọ́n..
wikipedia
yo
Orúkọ ọmọ sábà máa ń wá láti ọ̀dọ̀ àwọn òbí méjèèjì ìyá àti bàbá ọmọ àti àwọn òbí tó bí òbí méjèèjì yí wọn bí ọmọ tí wọ́n fẹ́ sọ lórúkọ..
wikipedia
yo
Orúkọ ìbílẹ̀ tí a dÍfá fún láti ọ̀dọ̀ babaláwo ń ṣe àfihàn òrìṣà tó ń ṣe atọ́nà ọmọ náà wá sáyé, yálà ọmọ náà jẹ́ àtúnbí óònílé àti pé kádàrá ọmọ àti nípa ti ẹ̀mí tí ó lẹ́tọ̀ọ́ sí, tí ó máa ran ọmọ lọ́wọ́ láti lè jẹ́ kí ó tẹ̀ ẹ́ lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Ayẹyẹ ikọkọ akọkọ kan tun wa fun iya ati baba ọmọ nikan nibi ti orukọ ati èèwọ̀ yoo ti maa jẹ fifun ọmọ ati obi rẹ, ati aba lori ohun ti ọmọ naa maa nilo lati fi ṣe aṣeyọri..
wikipedia
yo
Ọjọ́ díẹ̀ lẹ́yìn ìnáwó àwùjọ tí àṣẹ àti àríyá ti wáyé tí ebi àti ojúlùmọ̀ sì ti jẹ́ ìpè àwọn òbí ọmọ láti wá báwọn ṣàjọyọ̀ ìbí ọmọ náà.àròkọ àti ìwúlò orúkọọ̀rukò Yorùbá jẹ́ ohun tí ènìyàn máa ń ṣáábà kíyèsí láàrin ọ̀sẹ̀ ṣáájú ayẹyẹ ìsọmọ-lórúkọ gẹ́gẹ́ bí i àbójútó nlá tí ó wà lórí gbígbé e lórí i yíyan orúkọ kan tí kò ní ìrísí lórí èyíkéyìí ìwà tó lòdì tàbí ìwà búburú láàrin àwùjọ,ni ó mìíràn yíyan orúkọ tí ó ti ọ̀daràn kan tẹ́lẹ̀ fún ọmọ Yorùbá kan kìí jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà gẹ́gẹ́ bí èrò Ọlọgbọ́n (gẹ́gẹ́ bí i ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ èrò Yorùbá) lè mú kí ọmọ náà ó di olè tàbí ọ̀daràn lọ́jọ́ iwájú.Ìpín sí ìsọ̀rí orúkọ Yorùbá àyànmọ́ èyí ni a tún mọ̀ sí orúkọ àmútorúnwá, (orúkọ tí a gbà wí pé àti ọ̀run ni a ti gbé e wá tàbí tí a ti jẹ́ bọ̀ láti) àpẹẹrẹ ni Àìná, Iwín, * yẹ, òye, Táíwò, gọ̀, Gogo, Babátúndé, Babátúndé, Jówín, ìpá, àbíọ́nà, Olùdo, ìFR, Yéwándé èyí ni (orúkọ tí a fún ọmọ ní ọjọ́ tí an ṣàjọyọ̀ ibi rẹ̀, yálà látẹnu àwọn òbí rẹ̀ ni tàbí àwọn alá-ún mọ-un fún un) ni a tún ń pè ní orúkọ àbísọ..
wikipedia
yo
Èyí sábà máa ń jẹ mọ́ ipò tí ẹbí tàbí àwọn òbí ọmọ náà wà ní àwùjọ..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ ni ẹ̀yinfúnjọ̀wọ́, ẹ̀yinafe, Ajilarán, ajíSafe, ọ̀pẹ́lẹ́ńgẹ́, arikúyẹrí, agbọ́kúnítì, awẹlẹ́wà, ìbádia àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Meji ninu orukọ àmútọ̀runwá Yorùbá tó gbajúmọ̀ jù ni Taiwo (tàbí Taye) ati Kehinde ti wọ́n fún àwọn ìbejì ní pàtàkì..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ìgbàgbọ́ pé àkọ́kọ́ nínú ìbejì ni Taiwo (tàbí Taye) ti ó gbèrò láti kọ́kọ́ jáde wá sáyé láti ‘‘fínlẹ̀ bóyá agbègbè ibi tí wọ́n fẹ́ wò dára tàbí kò dára láti wá sínú ẹ̀..
wikipedia
yo
Tí ó bá tẹ́ ẹ lọ́rùn a tẹ́wọ́ gba Ikeji rẹ̀ Kehinde (nígbà mìíràn a dá Kehinde padà) kò ní kó má a bọ̀..
wikipedia
yo
Ó ṣeéṣe fífún ọmọ tí wọ́n máa kọ́ gẹ́gẹ́ bí i babaláwo àti iṣẹ́ Ifá máa jẹ́ kí ó dọlọ́rọ̀ àti aláṣeyọrí..
wikipedia
yo
Àwọn òbí onigbagbọ ìgbàlódé fún iṣẹ́ kí wọ́n máa lo orúkọ àbáláyé fún pípààrọ̀ orúkọ òrìṣà fún Olú tàbí Olúwa, ìtumọ̀ Olúwa tàbí Olúwa mi tí ó ń tọ́ka sí èròǹgbà onígbàgbọ́ nípa Ọlọ́run àti Jesu Kírísítì..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ olùwáti-OLUWA ti ṣe,àwọn òbí gbadura fún ọmọ OLUWA náà sì fún wọn nìkan..
wikipedia
yo
Àwọn òbí mùsùlùmí máa ń fẹ́ fẹ́ fún ọmọ wọn ní orúkọ Lárúbáwá nígbà mìíràn pẹ̀lú pípè Yorùbá, Ràbùkùbẹ́ẹ̀ di ráfíFI..
wikipedia
yo
Orúkọ Ipasẹ̀ tún lè ṣàkàwé ipò ti Ìdílé náà wà láwùjọ (àpẹẹrẹ “Adewale” orúkọ ìdílé ọba àtàtà) Ó tún lè ṣàkàwé iṣẹ́ abínibí Ìdílé kan (àpẹẹrẹ “A”, àwọn alágbẹ̀dẹ)..
wikipedia
yo
Yorùbá tún ni oríkì irú èyí tí àwọn àkòríkí máa ń lò láti tẹpẹlẹ mọ́ àṣeyọrí aṣáájú ti oríṣìíríṣìí ìdílé..
wikipedia
yo
Oríkì tún lè jẹ́ ẹlẹ́yọ ọ̀rọ̀ bí i "Àdùnní"tàbí kí ó jẹ́ ẹsẹ ìwé tàbí jantirẹrẹ..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé kì í ṣe ipa àtàtà ni ó ń kó nínú orúkọ gidi, oríkì máa ń sábà jẹ́ lílọ ní ẹgbẹ́ kan, ó máa ń sábà jẹ́ ohun tí gbogbogbò mọ̀ mọ́ọ̀yàn ní àkókò kan..
wikipedia
yo
Púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn ní àwọn ará ìlú mìíràn lè dámọ́ kódà ìdílé wọn nípa lílo oríkì òkun ìrandíran wọn.Iṣẹ́ kékeré ni yíyan orúkọ nísin yìí, nítorí kò sí àkójọpọ̀ orúkọ Yorùbá tó pè..
wikipedia
yo
Síbẹ̀síbẹ̀ iṣẹ́ àgbéṣe titun látọwọ́ akẹ́kọ̀ọ́ èdè Nàìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ láti ṣe gbogbo orúkọ Yorùbá sí kíkọ sílẹ̀ sínú ìwé Aridìí ní ti ìlànà onírúurú ọnà ìgbàròyìn.Orúkọ Yorùbá náà ni ìwé yìí dá lé..
wikipedia
yo
Ó sọ̀rọ̀ nípa jíjẹ́ orúkọ, ètò ìkómọjáde, orúkọ àmútọ̀runwá, orúkọ àbísọ àti orúkọ aralórí wọn ń fún Àbíkú, ìyàtọ̀ láàrín orúkọ àti alájẹ̀ kí ó tó wá fi orílẹ̀ parí rẹ̀..
wikipedia
yo
Awon itumo awon oro ti ta koko naa si wa pelu.Àwọn itọkasic.L..
wikipedia
yo
aṣitẹ́ęki-àánùanuAztec-an\ẹgbẹ́ èdè kan tí ó ní ọgbọ̀n èdè nínú ni a n pè ní Azter-an..
wikipedia
yo
Wọ́n ń ṣọ́ ọ ní ìwọ̀-oòrùn àti gúsù ìwọ-oòrùn Amẹ́ríkà (USA)..
wikipedia
yo