cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àwọn èdè tí ó wà ninu ẹgbẹ́ yìí ni Comanche, Paitété Shoshone ati Hopi..
wikipedia
yo
Àwọn mẹtẹẹta náà ní nàhuat (tí wọ́n tún ń pè ní Aztec; ó ní ẹ̀yà pupọ..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń ṣọ́ wọn fẹ́rẹ̀ẹ́ tó mílíọ̀nù kan àbọ̀ 1.4..
wikipedia
yo
Pápá-gò-má ti ẹgbẹ̀rún méjìlá ènìyàn ń sọ ní ẹ̀kẹta..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn èdè yìí ni ó ń lo àkọsílẹ̀ Romaanu (Roman Alphabet)..
wikipedia
yo
AzỌrẹ ikaniyan 1995 sọ pé ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogójì lé ní igba ènìyàn ló ń gbé Azores..
wikipedia
yo
Wọ́n ti ń lo èdè Gẹ̀ẹ́sì báyìí sí i sá fún èdè ìgbafẹ́ (Tourism). Àwọn orílẹ̀-èdè Europe..
wikipedia
yo
Èdè Azerkaogójìọmọ ẹgbẹ́ ní èdè yìí jẹ́ fún ẹgbẹ́ èdè tí à ń pè ní Turkic..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń sọ Azerbáoṣù tó mílíọ̀nù mẹ́rìnlá ní Azerbaijan ní ibi tí wọ́n ti ń lò ó gẹ́gẹ́ bí èdè iṣẹ́ ìjọbí..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ń sọ èdè yìí ní Turkey, sýríà àti AFglotanus..
wikipedia
yo
Àkọtọ́ Cyrillic ni wọ́n fi ń kọ ọ́ sílẹ̀ ní Azerbaijan ṣugbọn akoto Arabic ni wọ́n fi ń kọ ọ́ sílẹ̀ ní ìran..
wikipedia
yo
Wọ́n fi ojú ẹ̀dà èdè pín wọ́n sí Swuphile Azerkaoṣù) àti Northern Azerbáoṣù ti mílíọ́nù méje ènìyàn n ṣo.Ìtọ́kasí àwọn èdè..
wikipedia
yo
Aaṣeïba ni ètò ìkànìyàn 1995, àwọn tí ó ń sọ èdè yìí jẹ́ Milionu méje àbọ̀..
wikipedia
yo
Òun ni ó jẹ́ èdè ìjọba fún àṣeroṣùoṣù níbi tí àwọn ìdá mẹta ninu mẹrin àwọn tí ó ń gbé ibẹ̀ ti ń sọ ọ́..
wikipedia
yo
Àwọn ìdá mẹ́fà nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tí ó ń gbé Rọ́ṣíà ni ó ń sọ èdè yìí..
wikipedia
yo
Àwọn èdè bu mejila mìíràn tún wà èyí tí Avar àti Armerican wà lára wọn.Ìtọ́kasí àwọn orílẹ̀-èdè Europe..
wikipedia
yo
queríbù fún náà jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ fún àwọn èdè Andeadea-Equatorial..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń sọ àwọn èdè wọnyi lé díẹ̀ ní mílíọ̀nù meji (2.2.million)..
wikipedia
yo
Pupọ ninu àwọn tí ó ń ṣọ́ wọn wà ní Bolivia (1.8 million) ó dín díẹ̀ ní mílíọ̀nù meji..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ń sọ àwọn èdè wọ̀nyí ní Peru àti apá kan Argentina..
wikipedia
yo
Ni igba kan ri, Aymara je ede kan ti o se pataki ni aarin gbùngbùn Andes ti won je apa kan enipáyà Inca (Inca Empire)itọkasi..
wikipedia
yo
AfaaruAvarómo ẹgbẹ́ àwọn èdè tí wọ́n n pè ní Dáges ni eléyìí..
wikipedia
yo
Danges yìí tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ẹgbẹ́ fún àwọn tí wọ́n ń pè ní Caucasicasian..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń sọ Caucasian yìí tó ẸGBẸ̀RÚN LỌ́NÀ ẹgbẹ̀ta ní Caucasus ní pàtàkì ní Ìpínlẹ̀ dageus ní Rọ́ṣíà àti Azerbaijan..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀yà ní àdúgbò yìí ni wọ́n ń lò wọ́n gẹ́gẹ́ bí èdè ìṣèjọba..
wikipedia
yo
Àwọn andi àti dídó náà wà lára àwọn ẹ̀yà tí ó ń lò wọ́n.Àwọn èdè..
wikipedia
yo
Ositiro-esíatiìkìustro-ásìàtiàwọn èdè tí ó wà nínú ẹbí èdè yíi tó àádọ́sàn-án..
wikipedia
yo
gulẹ ila-oorun Asia ni pataki ni China ati INDONESIA ni wọ́n ti ń so wọ́n jù..
wikipedia
yo
Àwọn kan sì tún ń ṣọ́ wọn ní apá ìwọ̀-oòrùn àríwá India àti ní erékùṣù Nicọbar (nicr Island)..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà mẹ́ta ẹbí èdè yìí tí ó ṣe pàtàkì ní Mon-Khdmer (tí ó jẹ́ pé nínú rẹ̀ ni àwọn èdè pọ̀ sí jù), múnda àti níyìnrese..
wikipedia
yo
Àwọn méjèèjì tó gbẹ̀yìn yìí ni wọ́n ń sọ ní ìwọ̀-oòrùn àdúgbò Mon-Khd..
wikipedia
yo
Láti fi ìmọ̀ ẹ̀dà èdè pín àwọn èdè yìí sọ̀rọ̀ díẹ̀ nítorí pé díẹ̀ nínú àwọn èdè yìí ni ó ní àkọsílẹ̀ àti pé ìbáṣepọ̀ tí ó wà ni àárín àwọn ẹbí èdè yìí àti àwọn ẹbí èdè mìíràn kò yé èèyàn tó…
wikipedia
yo
Australia (, or ), fún ibiṣẹ́ bi orílẹ̀-èdè àjọni ilẹ̀ Australia, jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Southern Hemisphere tó ní gbogbo ilẹ̀ orílẹ̀ Ofìfẹ́ (tó kéré jùlọ láyé), Erékùṣù Tasmania, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Erékùsù kékèké ní inú okùn India àti pàsífìkí..
wikipedia
yo
Awon orile-ede to ni Bode pelu ni INDONESIA, East Timor, ati PAPUA New Guinea ni ariwa, Solomon Islands, Vanuatu, ati New Caledonia ni ariwa-ilaọrun, ati New Zealand ni guusuilaọrun.itọkasi awon orile-ede ose oseíà..
wikipedia
yo
Osireliakaustroanaustrolian ni a orúkọ fún ẹgbẹ́ àwọn èdè kan tí àwọn Aborigine ń sọ..
wikipedia
yo
Àwọn èdè yìí fi bí ọ̀bọ̀n lé ní igba (230) síbẹ̀ àwọn tí ó ń ṣọ́ wọn kò ju ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n lọ..
wikipedia
yo
Wọ́n pín àwọn èdè wọ̀nyí sí ẹbí bí ọgbọ́n ó dun méjì nítorí wí pé wọ́n ní wọ́n bá ara wọn tan..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn èdè wọ̀nyí, yàtọ̀ sí ọ̀kan nínú wọn ni ó wà ní àríwá ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Australia àwọn ilẹ̀ tí ó wà ní àríwá (Northern Territory) àti Queensland..
wikipedia
yo
Gbogbo ilẹ̀ tí a ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí kò ju ìdá mẹ́jọ ilẹ̀ Austrolia lọ..
wikipedia
yo
Ṣugbọn èdè tí à ń pe ẹbí rẹ̀ ní Pa-MA-Wyun ni ó gba gbogbo ilẹ̀ yòókù ní Austrolíà..
wikipedia
yo
Àwọn èdè tí ó wà nínú ẹbí yìí tó àádọ́ta tí àwọn ènìyàn sì ń lò wọ́n dáadáa..
wikipedia
yo
Àwọn èdè tí àwọn eniyan ń sọ jù ni Twi, Wapírí, Aranda, mabuyng ati Western Desert..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń ṣọ́ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn lé tàbí kí ó dùn díẹ̀ ní ọgọ́rùn-ún..
wikipedia
yo
Láti nǹkan Buńláẹ́ń kejidun àwọn èdè tí ó ní àwọn tí ó ń ṣọ́ wọn tí ń dínkù jọjọ..
wikipedia
yo
Púpọ̀ nínú àwọn tí ó ṣẹ̀kí yìí tí ń parẹ́.Kò sí ẹni tí ó lè sọ bí ọjọ́ iwájú àwọn èdè Aborigine yìí yóò ṣe rí ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn tí ń ṣiṣẹ́ gidigidi lórí wọn báyìí láti nǹkan bí ọdún 1960 tí àwọn kan ti dìde láti jà fún fífún gbogbo ènìyàn ní ẹ̀tọ́ lábẹ́ òfin..
wikipedia
yo
Púpọ̀ nínú àwọn èdè wọ̀nyí ni ó ti ń ní àkọsílẹ̀ tí wọ́n fi àkọtọ́ Romaãnú (Roman Alphabet) kọ..
wikipedia
yo
Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ sì ti ń lo èdè méjì., Èdè mìíràn àti èdè mìíràn...
wikipedia
yo
Ẹ̀sìn ìmàle tàbí ẹ̀sìn Islam ( , ) jẹ́ ẹ̀sìn àlàáfíà,ìrọ̀rùn àti ijùpa-jù sílẹ̀ fún Ọlọ́run Aṣẹ̀dá gbogbo ayé nípa ṣíṣe ìfẹ́ àti títẹ̀lé àṣẹ rẹ̀ yálà ó tẹ́ ọ lọ́rùn tàbí kò tẹ́ ọ lọ́rùn..
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ ẹ̀sìn tí Ọlọ́run tún fi ránṣẹ́ sí gbogbo ayé látọwọ́ àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀ tó ti rán wá ṣáájú Anọbi Muhammad ọmọ Abdullah (kí ìkẹ àti ọlá olóhùn ó má ba )..)..
wikipedia
yo
Òun sì ni ẹ̀sìn òtítọ tí ẹ̀sìn mìíràn kò le jẹ ìtẹ́wọ́gbà ní òdò olóhun (Allah) yàtọ sí Òun nìkan..
wikipedia
yo
Ọlọhun (Allah) sì ti ṣe é ní ẹ̀sìn ìròrùn tí kò sí ìṣòro kankan tàbí wahala níbẹ̀..
wikipedia
yo
Kò sí ohun tí ó kọjá agbára wọn, bẹ́ẹ̀ sì ni kò sì ìjẹ́ni nípa fún àwọn tí wọ́n gba ẹ̀sìn náà..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ sì tún ni ẹṣin náà kò la ohun tí ó kọjá agbára wọn bọ̀ wọ́n lọ́rùn..
wikipedia
yo
ISIdù ni ẹṣin tí ó ṣe pé ìmọ̀-olóhun ni (Al- Tao) ni ìpìlẹ̀ rẹ̀, òdodo ni ọ̀pọ̀ rẹ̀, ó dá lórí déédé,òtítọ́..
wikipedia
yo
Ohun sì ni ẹ̀sìn tí ó gbópọn tí ó jẹ́ pé ó ń darí gbogbo ẹ̀dá sí ibi gbogbo ohun tí yóò jẹ́ àǹfààní fún wọn ní ọ̀run àti ayé wọn..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni ó sì tún ń kì wọ́n nílọ̀ nípa gbogbo ohun tí yóò sáburú fún wọn yálà láyé ni tàbí ọrun..
wikipedia
yo
ohun ni ẹ̀sìn ti Ọlọhun (Allah) fi ṣe àtúnṣe àwọn Adi-ọkàn àti àwọn ìwà àìdáa kan..
wikipedia
yo
ohun náà ni O fi ṣe àtúnṣe iṣẹmi ayé àti ti ọrun..
wikipedia
yo
Òun ni olóhun (Allah) fi ṣe ìrẹ́pọ̀ láàrin àwọn ọkàn tí ó kẹ̀yìn sí ara wọn àti àwọn ojúkòkòrò tí ó fọ́nká..
wikipedia
yo
Nípasẹ̀ èyí ni ó fi yọ àwọn ohun tí a kà sí iwájú yìí nínú òkùnkùn biribiri irọ́, tí ó sì ṣe ìfinimọ̀nà rẹ̀ lọ sí ibi òtítọ́, tí ó sì tọ́ ọ sí ọ̀nà lọ sí ibi ọ̀nà tí ó yè kooro.
wikipedia
yo
Esin Islam jẹ́ orúkọ iṣẹ́ Ayélujára gbajúgbajà ti Sheikh Dr..
wikipedia
yo
Abdul-Fattah Ademọla ẹni tí í se olórí àti olùdásílẹ̀, àwq Africa àti aṣíwájú ẹ̀sìn fún àwọn aláwọ̀ dúdú ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì dá sílẹ̀ láti ipasẹ̀ Èsìni,com fún ẹ̀kọ́ nípa ẹ̀sìn Islam pẹ̀lú àwQafaf Africa Muslim Open College ní ìlú London.Ẹṣin Islam ní ṣókí Islam ní ẹ̀sìn tí ó dúró tó, èyí tí a gbé kalẹ̀ ní ọ̀nà tí ó dára dé òpin nínú gbogbo àwọn ìró tí ó múwá àti nínú gbogbo àwọn ìdájọ́ rẹ̀ pátá.Kò sí ìròyìn kankan nínú rẹ̀ àyàfi òtítọ́ àti òdodo bẹ́ ẹ̀ sì ní kò sí ìdájọ́ kankan nínú rẹ̀ àyàfi rere àti déédé..
wikipedia
yo
èyí yó o jẹ bẹ̀ ẹ́ nípa ṣíṣe ohun tí o ṣe ní ọ̀ranyàn lé wọn lórí nínú àwọn àṣẹ àti (jíjìnnà sí) àwọn ohun tí o kò fún ni láti ṣe..
wikipedia
yo
Èyí túmọ̀ sí pé òun ni Ọba,oluda, Oluni ati Olùṣàkóso gbogbo àwọn ètò (ayé ati ti ọ̀run ).
wikipedia
yo
(ii) Níní ìgbàgbọ pẹ̀lú pé Ọlọhun (Allah) nikan ni Atoọ̀sin..
wikipedia
yo
Èyí túmọ̀ sí pé òun nìkan ni ó ní ẹ̀tọ́ láti máa gba ìjọsìn àti pé ẹlòmíràn tí a bá darí ìjọ́sìn sì yàtọ̀ sí òun jásí ìgbésẹ̀-ìkùnà tí kò tọ́.
wikipedia
yo
(iii) Níní ìgbàgbọ́ nínú àwọn orúkọ rẹ̀ àti àwọn oríkì rẹ̀..
wikipedia
yo
Èyí túmọ̀ sí pé òun ni ó ni àwọn orúkọ tí ó dára jùlọ àti àwọn oríkì tí ó pé pérépéré tí ó sì ga jùlọ gẹ́gẹ́ bí ó ti wà nínú tirara rẹ̀ (Al -Quran) àti Sunah (ìlànà) òjíṣẹ rẹ̀ (kí ìkẹ àti ọlá olóhun kí ó má a baà).2) níní ìgbàgbọ nínú àwọn mọláàpọn àwọn mọláàpọn ní àwọn ẹrú olóhùn kan tí wọ́n jẹ́ ẹni àpọnlé gẹ́gẹ́bí wọn ti jẹ ẹ̀dá olóhùn (Allah)..
wikipedia
yo
Bákannáà, wọ́n jẹ́ olùṣe ìbáàdá (ijọ́sìn) fún olóhùn dé ojú àmì wọ́n sì tún jẹ́ àtẹ̀lé àṣẹ rẹ̀ ní pérépéré..
wikipedia
yo
Ọlọhun (Allah) fi àwọn iṣẹ (ojúṣe) oríṣìríṣìí fún ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn..
wikipedia
yo
nínú wọn ní Jibiriìlú ẹni tí a ṣe Áfítì iṣẹ mímọ́ tí ó bá n wáyé láti ọ̀dọ̀ olóhùn (Allah) sí ọ̀dọ̀ ẹni tí ó bá fẹ̀ nínú àwọn ànábì rẹ̀ àti àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀ ti sí..
wikipedia
yo
Ara wọn sì tún ni míìkaìlú ẹni tí ó wà fún Alaarí rírọ òjò àti àwọn koríko tí ń hù..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni ara wọn ní Ìsíraìlú ẹni tí ó wà fún fífọn fẹ́re ní àsìkò tí olóhun (Allah) bá fẹ́ kí gbogbo ẹ̀dá ó sun oòrùn àsùn- fọnfọn- ń-fọ́n-fọ́n tí yóò kásẹ̀ ilẹ̀ ayé nílẹ̀ àti nígbà tí ó bá tún fẹ́ kí wọ́n dìde (láti jábọ̀ nípa ìgbésí ayé wọn)..
wikipedia
yo
Ara wọn sì tún ni moláìka ikú ẹni tí ojúṣe rẹ̀ jẹ́ gbígba àwọn ẹ̀mí ní àsìkò tí olóhùn (Allah) bá ti ní àsìkò rẹ̀ tó.(3) níní ìgbàgbọ sí àwọn Ìwé Mímọ́ olóhùn (tira) olóhùn (Allah), Ọba tí Ô tôbi tí O sì gbọn-un -gbọn jùlọ sọ àwọn ìwé kalẹ̀ fún àwọn Òjíṣẹ Rẹ̀ ẹ̀yí ti ònà Mímọ, rere àti dáradára wà nínú Rẹ̀..
wikipedia
yo
tira yi ni iwe ti o tobi julọ ti o sọ kalẹ̀ fun awọn ọmọ Isialáápọn.
wikipedia
yo
(ii) Injiila (Bíbélì) ti Ọlọhun (Allah) sọ kalẹ̀ fun Anabi isà ẹni ti àwọn kan mọ si jẹẹ̀ṣù- (kí ike ati ọlá Ọlọhun o ma a baa).
wikipedia
yo
(iii) Sbuura ti Ọlọhun (Allah) sọ kalẹ̀ fun Anabi dáṣéúdà -ẹni tí àwọn kan mọ̀ sì dáìdí - (Kí iké àti ọlá olóhun ó máa báa) (iv) àwọn tàkàá (Ewe ’Q) ti olóhùn (Allah) sọ̀ kalẹ̀ fún ẹ -kejì Ànábì Anabiìmọ - ẹni tí àwọn kan mọ̀ sí abúraHáàmú - àti Ànábì Musa..
wikipedia
yo
(v) alukuraani alapopo eyi ti Ọlọhun (Allah) ti ọla rẹ ga julọ sọ kalẹ̀ fun Anabi rẹ ti n jẹ Muhammad ẹni ti i se olùpinnu awọn Anabi .tira alapopo yii ni Ọlọhun (Allah) fi fagile gbogbo awọn iwe mimọ ti o ti sọ kalẹ̀ siwaju rẹ..
wikipedia
yo
Ìdí abájọ èyí ni ó mú kí olóhùn fúnraàrẹ mójútó ṣíṣọ́ tira náà (kúrò níbíi àfikún tàbí àyọkúrò ọmọ adáríhunrun tàbí sísọnù) nítorípé òun ni yóò ṣekú gẹ́gẹ́bí àwíjàre tí ó fẹsẹ̀ múlẹ̀ gbọn- in -gbọn-in fún gbogbo ẹ̀dá títí di ọjọ́ ìgbẹ̀hìndé (Alikiyàá).(4) níní ìgbàgbọ́ sí àwọn òjíṣẹ́ olóhun pátá láìkò dá ẹnìkan sí Olóhùn (Allah) ti rán àwọn òjíṣẹ́ kan sí àwọn ẹ̀dá rẹ̀.Ẹni àkọ́kọ́ nínú àwọn òjíṣẹ́ náà ni Ànábì Nuhu nígbàtí nínú Olùṣọ́Hailad (Kí iké àti ọlá olóhun ó má a baà àti gbogbo àwọn òjíṣẹ́ tí ó ṣíwájú rẹ̀)sì jẹ́ olùpinnu wọn..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn òjíṣẹ́ olóhùn pátá –tí ó fi mọ́ Ànábì ìṣà- jẹ́ ẹ̀dá abara tí kò sí nkankan ninu jíjẹ olóhun ní ara wọn..
wikipedia
yo
Àwọn pàápàá jẹ ẹrú olóhun (Allah) gẹ́gẹ́bí àwọn ẹ̀dá yókù náà ti jẹ́ ẹrú olóhun ṣùgbọ́n ti tàbí wọn ṣe àpọnlé fún wọn pẹ̀lú rírán wọn ní ìṣe mímọ́ sí àwọn ẹ̀dá abara yó..
wikipedia
yo
Ní àkótán, olóhun (Allah) ti parí gbogbo iṣẹ́ tí ó fẹ́ rán sí ayé pẹ̀lú ìṣe-ìmọnà tí ó fi rán Ànábì Muhammad (kí ìkẹ́ àti ọlá olóhun ó máa báa).O sì ti rán an sí gbogbo ẹ̀nìyàn láìkò dá ẹnìkan sí..
wikipedia
yo
Nítorí náà, kò sí Ànábì kankan mọ́ lẹ́yìn Ànábì Muhammad (kí ìkẹ́ àti ọlá olóhun ó máa báa).(5) níní ìgbàgbọ́ nípa ọjọ́ ìkẹhìn ọjọ́ agbédèdè ní ọjọ́ ìkẹhìn tí kò ní sí ọjọ́ kankan lẹ́yìn ọjọ́ náà mọ́..
wikipedia
yo
Ọjọ́ náà ni olóhun (Allah) yóò gbé gbogbo ènìyàn dìde ní ààyè padà láti ṣẹ́kù títí ayérayé nínú ilẹ̀ onídẹ̀ra (úbín)tàbí nínú ilé ìyá (iná) kàyéfì.Nínú ìgbàgbọ́ sì ọjọ́ ìkẹhìn jásí níní ìgbàgbọ́ sí gbogbo ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ikú ní èyí tí ó kọ ìbéèrè (fitino) ṣááẹ̀ àti ìdẹ̀ra pẹ̀lú ìjìyà rẹ̀ sínú..
wikipedia
yo
Ati ohun ti yoo tun ṣẹlẹ leyin eléyìí gegebi agbedèdè, iṣẹpadabo si ọdọ Ọlọhun ati iṣiro iṣe ti ẹda gbe aye se..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn-ìgbá-náà, ni ìmọ́rilẹ̀ ilẹ̀ ibùgbé ayérayé èyí tí í ṣe àlùpòwo tàbí ina.(6) níní ìgbàgbọ sí kadara(Àkọpìwàdà) ohun tí òún n jé kádàrá ni níní ìgbàgbọ pe Ọlọhun (Allah) ni ó pebúbú gbogbo ohun tí ń bẹ, ohun ni ó sì dá gbogbo ẹ̀dá ní ọ̀nà tí mímọ́ rẹ̀ ti ṣíwájú rẹ̀ ti àríwòye rẹ̀ sì fẹ́ bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn Alaarí ni ó ti jẹ́ mímọ́ ni ó sì tì wá ní àkọọ́lẹ̀ ní ọ̀dọ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
ìjẹ́rĩ yìí ní kòkòrò Islam àti ìpilẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ tí gbogbo ẹ̀ka yókù dúró lé lórí.Ìtúmọ̀ a i sí ọba míràn lẹ́yìn olóhun (Allah) ni pé kò sí ẹni tí ó lẹtọ pé kí a má a ṣe ìjọsìn fún ju òun nìkan lọ.Òun nìkan ní àpésìn tòótọ́..
wikipedia
yo
Gbogbo ẹlòmíràn tí a bá ń darí ìjọ́sìn sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ yàtọ̀ sí òun jẹ́ ìwà ìbàjẹ́ tí kò sì lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ bí ó ti wù kí ó mọ..
wikipedia
yo
Ohun tí ó ń jẹ́ olóhùn ọba ninu àgbọ́yé àwa mùsùlùmí ni ẹni tí à á jọ́sìn fún.Ìtumọ̀ ìjẹ́rĩ (ifaramọ) pé Ànábì Muhammad (kí iké àti ọlá olóhun ó máa bàá) jẹ́ òjíṣẹ́ olóhun ní gbígbà á ní òdodo nínú gbogbo ohun tí ó fún ni ní làbárè rẹ̀, títẹ̀lé e nínú gbogbo oun tí ó pa láṣẹ àti jíjìnnà sí gbogbo ohun tí ó kọ́ fún ni láti ṣe tí ó sì jágbe mọ́ a í fẹ́ bẹ́ ẹ̀.Irun kíkí èyí ni àwọn irun tí a má a ń pààrà kíkí rẹ̀ ní ẹ̀ẹ̀marùn lójúmọ́..
wikipedia
yo
Olóhùn (Allah) ṣe é ní òfin láti leè jẹ ìfun olóhun ní ìwọ ó rẹ lórí àwọn ẹrú rẹ, ìdúpẹ́ fú un lórí ììnírà rẹ àti okun ìdàpọ̀ láàrin Mùsùlùmí àti olóhun Àǹfàànílélẹ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
èyí tí yóò má a bá a ní gbólóhùn nínú rẹ̀ tí yóò sì má a gbàdúrà sí i nínú rẹ̀..
wikipedia
yo
Ti àwọn ìrun yìí yọ o sì jẹ ákín fún un nípa ṣíṣe ìbàjẹ àti ṣíṣe aburú.olóhun (Allah) sì ti ṣe dánilójú dáradára ẹ̀sìn, ìgúnrégé ìgbàgbọ àti Laada ayé àti ti ọrùn fún ẹni tí o bá n kí ìrun wákàtí márààrún dáadáa..
wikipedia
yo
Ní ipasẹ̀ àwọn irun yìí ni ìbàlẹ̀-ọkàn àti ìbàlẹ̀-ara tí yóò jẹ́ okùnfà oríre ayé àti tí ọ̀run yóò fi ṣẹlẹ̀ fún ẹni tí ó bá ń kìí déédé.Iore àánú (Saka) èyí ni ọrẹ àtinúwá kan tí ẹni tí ó bá ní owó tí ó ti wọ gbèdéke tí ìlànà Islam ṣe àfilélẹ̀ rẹ̀ yóò má a san ní ọdọọdún fún àwọn ẹni tí o létò sí gbígbà rẹ̀ nínú àwọn aláìní àti àwọn míràn..
wikipedia
yo
A ní láti mọ̀ dájú gbangba pé ìtọrẹ àánú yí i kò jẹ́ dandan fún aláìní tí kò sì gbèdéke òwò yìí ní ọwọ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ẹni tí ó jẹ́ dandan fún ni àwọn ọlọ́rọ̀ tí yóò jẹ́ pípé fún ẹ̀sìn wọn àti ìfara Islam wọn .Tí yóò sì tún mú ìlọsíwájú bá ìwàsí wọn àti ìhùwàsí wọn pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Èyí sì tún jẹ́ ọ̀nà kan pàtàkì láti mú ìyọnúsí àti ìyójú ayé kúrò lára wọn àti lára dúkìá wọn..
wikipedia
yo
ati láti ṣe àfọ̀mọ́ fún wọn kúrò níbi aburú pẹlu láti ṣe ikùnlọ́wọ́ fún àwọn tálákà ati àwọn aláìní láwùjọ ati láti ṣe ìgbédúró ohun tí yóo mú nkan tùbàtú fún àwọn gan an alára pàápàá..
wikipedia
yo
Paríparí gbogbo rẹ̀, oore àánú yìí kò kọjá ẹ̀bùbù kan kínkinní nínú ohun tí olóhun (Allah) ṣe fún wọn nínú òwò àti ìjẹ- imú.Ààwẹ̀ gbígba eléyí yòò má a jẹ ohun tí yòò má a ṣẹlẹ̀ nínú oṣù kan ṣoṣo lọ́dọọdún..
wikipedia
yo
Oṣù yẹn sì ni oṣù Ramadan ṣàánú, èyí tí ṣe oṣù kẹsan an ninu oṣù ọdún Hijira (ọdun ti a n fi òṣùpá mu ka)..
wikipedia
yo