cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní ilẹ̀ Áfíríkà, ó fẹ́ẹ̀ jẹ́ pé gbogbo èdè ni wọ́n ń lo OLUWA, abo ati ọ̀rọ̀ ìṣe..
wikipedia
yo
A tún máa ń lọ "less common word orders" nínú gbogbo èdè, láti ṣẹ̀dá gbólóhùn Ayísódì..
wikipedia
yo
(iyìces With Single Clauses) gbólóhùn aláwẹ́ kan.eto ọrọ (word Categories) àwọn ọ̀rọ̀ tí a máa ń tó pọ̀ di gbólóhùn ní or, iṣ, àpọnlé, èyàn àti atọ́kùn..
wikipedia
yo
Iwájú ọ̀rọ̀ orúkọ ni atọ́kùn máa ń wá Post position maa ń wà lẹ́yìn ọ̀rọ̀ orúkọ..
wikipedia
yo
Àwọn èdè Africa máa ń lo iṣ dáadáa ju àwọn èdè Gẹ̀ẹ́sì àti èdè àwọn European..
wikipedia
yo
-NGítì, Lendu, Central Sudanic, nilo-sohare -(ii)má M-ándi we are illewe, a le lo ọ̀rọ̀ ìṣe ní ibi tí àwọn elédè Gẹ̀ẹ́sì bá ti ń lo àpọnlé (E.G..
wikipedia
yo
Frely, not yet, still, again) ati ọrọ̀ asopọ (conJunction) E.G..
wikipedia
yo
And, their' -Yoruba, Defoisd, Benue - Congo, Niger- Congo (i)o tún ń lọ..
wikipedia
yo
-ẹjapham, Ekoid Bantu, Benue-Congo - Niger-Congo (ii)a-njan a-tẹ̀léd-a she is still Talkingàwọn èdè Africa kò ní atọ́ka púpọ̀ bí Europeans..
wikipedia
yo
Èdè Afirika jẹ́ èdè olóhùn, èyí ni a sì fi máa ń dá wọn mọ̀ yàtọ̀..
wikipedia
yo
(iii) s V Ó ADV tẹ́lẹ̀mẹ́ tẹ́lẹ̀ a pp ṕi Keneke ‘De' Dé ‘The monkey Caul the Branch Unce Ikeji tí ó tún gbajúmọ̀ ní ilẹ̀ Áfíríkà ní Aṣọ́n
wikipedia
yo
(iii)ALO, Maban, nilo-Saharan S Ó v Gop Yap Sam tarels ’The Farmer * A fiertile plot..
wikipedia
yo
A máa ń rí i ní Berber Chadiedi ní Afroásìati, nilotic Surmic ní ilẹ̀ eastern Sudamic..
wikipedia
yo
S Ó lọ̀c tọrọ ti GAàsí ga Ta gan gan tanke un joined its mother at the pound "X" yìí dúró fún ìkan lára àwọn àfikún..
wikipedia
yo
Àfikún (aduct) ní Location Post Posional phrase “ta GhamuAwon Ede Eru le lo Fasox fun afikun (adcts) bi a se rii ni Menade, pelu atọ́kùn Inmental prealáróonal a bo a ti o tumọ si with a knife..
wikipedia
yo
Ng, Western, nílẹ̀, Niger - Congo s Ó V Násì Ẹ wùrù Tẹ́ẹ a Bomber he stick cut with knife he cut the stick with a knife.Gbólóhùn àṣẹ àti ìbéèrè (Commands and Questions) ohun mẹ́ta ni a máa gbé yẹ̀wò..
wikipedia
yo
Èyí ìbéèrè ni tàbí bẹ́ẹ̀ kò (i) (Yes or no question) (2) Information Word question (3) inDirect Question..
wikipedia
yo
Nínú èdè Africa Yes/no question most commonly dissatisve only a question marker or morpheme at the end or the beginning of the láìmọ̀ces..
wikipedia
yo
Nínú èdè Africa ìbéèrè òní bẹ́ẹ̀ni tàbí bẹ́ẹ̀kọ́ máa ń ní àmì ìbéèrè ní ìbẹ̀rẹ̀ tàbí ìparí Linda is obìnrinú of many Niger-Congo and other langs, that use a question marker at the Edge of the sentence
wikipedia
yo
Linden i ògidì nínú àwọn Niger Congo tí ó ń lo ìbéèrè alámì ní òpin gbólóhùn..
wikipedia
yo
Linda, Banda, Adamawa -uTekoa, Niger-Congo (a)عce Gu he/she arrived she arrived (b)ce gu gu A/she arrived qmdid she arrive? Ninu èdè bíi Silte wón maa ń lo ohun gbigbe soke ní ìparí gbolohun, a lè lo o gege bii Yes/No question..
wikipedia
yo
Nínú èdè àwọn tàbípé, Gur ní ilẹ̀ Ghana, vowel or NASAl is irọ́tàbí and has a slow fall in Pittch..
wikipedia
yo
Èyí túmọ̀ sí pé nínú èdè tàbípé fáwẹ́lì tàbí àrànmúpè wọn máa ń falẹ̀..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹni díẹ̀ Saabu-uare You (pi) Eating PorRidge? Yes/No Question tún maa ń wáyé nípa lílo neòkúta (àyíd) "Did't he go to Accra? Nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì tí a bá dáhùn bẹ́ẹ̀ni, ohun tí a ń sọ ni pe ó lọ sí Accra..
wikipedia
yo
túmọ̀ sí pé oríṣìí àyísódì méjì ni á máa gbé yẹ̀wò..
wikipedia
yo
Ikeji, ó sì le jẹ́ àpólà kan nínú gbólóhùn bí àpólà orúkọ ni a máa yí sódì.verBal afFIFI ọ̀nà tí ó gbajúmọ̀ tí wọ́n fi máa ń yí gbólóhùn sódì ní ṣíṣe àtúnrọ àwọn ọ̀rọ̀ ìṣe..
wikipedia
yo
- AGSori, Grassfield, banú, Benue-Congo, Niger-Congo o bo fi - GHG he has hit the mat..
wikipedia
yo
Ó ká bó gbàm̀-fọ́ he has not hit the mat Compound and Complex 6ces (gbólóhùn ọlọ́pọ̀ àwé) Compound Sente-ní ṣíṣe awẹ́ méjì tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ pọ̀, ó máa ń jẹ odidi àwé àti àfara..
wikipedia
yo
Emphasis or Focus'àfojúsùn, àfojúsùn jẹ́ ohun pàtàkì tàbí Information Abẹ́nú nínú gbólóhùn..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ohun tí olùṣọ́ gbà pé oúgbọ́ kò gbọdọ̀ bá òun sọ..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ohun tí wọ́n sábàá máa ń lò ní (i) yíyí padà kúrò ní ọ̀rọ̀ ìṣe tàbí kí wọ́n lo aux aṣèrànwọ́ iṣẹ́ (2) use of special words (Parlọjọ́/ (3) Use of jolais-dínláàádóje constructions fún àpẹẹrẹ nínú èdè ẹjaGhana..
wikipedia
yo
(A)A - Nam BÍ-YU Buy Yamm "She bought yams(b)a - Nam-e Jẹ́n ​ Focus Focus What ​ ​ ​ .“ What What Did She She Buy (C)a - Nam-E bi-yu She bought ​ ​ ​ ​ yams yams èdè A Gchard ní àfojúsùn tó lé (Complex) in some * C uses a Focus (a Focus N Mo P Mo Moce N Ta ni The Rat Ran In the ComComgun Ggi..
wikipedia
yo
(b)Fu kí mo nyíp no a kì-be the rat ran (did not walk) in the compound (c)fu kí mo nyíp a kì-be no the rat ran inside the conpound (not inside the house)àwọn èdè mìíràn le lo apepo verb changes and Parlọjọ́, gẹ́gẹ́ bí ó ti hàn ninu èdè vute..
wikipedia
yo
(A)veve yí Gín-àjò-na ti P cene the Chief bought him a Chicken(b)Mve yí gín-àjò-na-a pge cene jáThe Chief bought him a Chicken...
wikipedia
yo
'Lọ́dúnso’’tsoso' jẹ́ òrìṣà àdáyé ba, tó jẹ́ pé tí wọ́n bá ti bí ọmọ àjàrà-tọpa, ìyá ọmọ náà kò ní jẹ iyọ̀ títí oṣù àfi yó lókè..
wikipedia
yo
Tí oṣù yìí bá ti yọ, wọ́n á gbé ọmọ náà bọ̀ sí ìta láti fi oṣù han ọmọ náà wí pé kí ọmọ náà wọ oṣù tí ó wá sáyé..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ náà ìyá ọmọ náà yóó gbé ọmọ náà bọ̀ sí ìta láìwọ aṣọ àti ọmọ náà pàápàá tí òun àti ọmọ rẹ̀ yóò sì jẹ iyọ̀ pẹ̀lú ẹja, wọn yóò sì tún fọ́ èkùrọ́ sórí ẹwà láti fún ìyá ọmọ náà jẹ nígbà méje tó bàjẹ́ obìnrin, ẹmẹsan-an tó bá jẹ́ ọkùnrin.Lẹ́yìn tí wọ́n bá ti ṣe èyí tán, ìyá ọmọ yóò gbé ọmọ rẹ̀ lọ sí ìdí òrìṣà ‘os’ láìwọ aṣọ ní ọjọ́ kejì, tí yóò sì ra ọtí dání láti súre fún ọmọ náà gẹ́gẹ́ bí àṣà..
wikipedia
yo
Wọ́n á sì padà sílé.Nígbà tí ìyá ọmọ náà bá dé ilẹ̀ yóò fá irun orí ọmọ rẹ̀, yóò sì lọ ra igba àti ìkókó tuntun..
wikipedia
yo
Omi odò yìí ni ìyá ati ọmọ yóo fi wẹ̀ títí omi yóo fi tán.Oriṣa yìí máa ń dáàbò bo àwọn ọmọde lọ́wọ́ aburú...
wikipedia
yo
Zantọ jẹ́ òrìṣà àwọn ẹ̀yà Ógù ní àgbádárìgì tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Badagry, tí wọ́n gbàgbọ́ pé ìran Yorùbá, ṣùgbọ́n tí wọ́n ṣe wá láti orílẹ̀ èdè Olómìnira Benin àti orílẹ̀-èdè Togo..
wikipedia
yo
Zantò lè jáde nígbà kúgbàá tí wọ́n bá fẹ́ ṣe ọdún òrìṣà tàbí ayẹyẹ ìbílẹ̀..
wikipedia
yo
'zanpọ̀ jẹ́ òrìṣà tó mọ́ ń pa idán ní ọjọ́ ayẹyẹ láti yẹ́ àwọn ènìyàn sí..
wikipedia
yo
'zangbé' sì tún jẹ́ ààbò fún ìlú kí àwọn ọlọ́ṣà máa bá wọ̀lú ní òru..
wikipedia
yo
Tí ọ̀rọ̀ kan bá sì ṣe pàtàkì, ‘píʹ kan náà ni wọn yóò rán láti lọ jẹ́ irú iṣẹ́ bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Tí ẹnìkan bá sì ṣẹ̀ tàbí lòdì sí òfin ìlú, àròkọ 'zanʹ ni wọ́n yóò fi ṣíwájú ilẹ̀ ẹ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá sì fi irú àròkọ yìí síwájú ilé rẹ̀ yóò ní láti dé ààfin ọba kí ó sì san ohun kóhun tí wọ́n bá ní kó sàn kí ó tó le wọ ilé rẹ̀.Àgbà gbàbọ̀ ọ̀rọ̀ níí ni pé àwọn ẹ̀sìn àtọ̀húnrìnwá wà ṣùgbọ́n ẹ̀sìn àbáláye kò lè parun, nítorí pé, gbogbo àwọn òrìṣà wọ̀nyí sì wà síbẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí Yorùbá..
wikipedia
yo
Idowu Oluwaṣeun Adesáyọ̀ìrìnàjò lọ sinu peoṣuPosuye mejo miran bii' ti wa lo n yi po kaakiri oorun..
wikipedia
yo
Àwa la sìkẹ́ta táa jìnà sóòrùn, àwọn méjì wà níwájú..
wikipedia
yo
Mo ní oòrùn tí à ń wọ̀ lókè táa rò pé ó kéré mo lọ tóbi lọ́pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà ju gbogbo ilẹ̀ ayé lọ báyé yìí ṣe ń yípo oòrùn, bẹ́ẹ̀ náà lóṣùpa ń yípo ayé mo tún sọ fún wa wípé jínjìn ilẹ̀ ayé sí òṣùpá tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́ọ̀rún mẹ́ta, ó lé ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún kìlómítà 320, 000 kìn..
wikipedia
yo
Bíi kéèyàn ó máa rin Èkó sí Ìbàdàn bíi ọ̀nà ẹgbẹ̀rún méjì bẹ́ẹ̀ náà lóṣùpa ṣe jìn sílẹ̀ ayé tó téèyàn bá kúrò lórí ilẹ̀ ayé àlàfo tí ń bẹ láàrin ilé-ayé àti òṣùpá, láàrin ilé ayé àti oòrùn láàrin ilé-ayé àti àwọn ayé mẹ́jọ tó kù lèèyàn ò kàn ó, téèyàn bá ń fò lọ sókè sínú òfurufú àlàfo yìí láwọn olóyìnbó ń pè ní Space ṣeé mọ̀ pé bí ìgbà téèyàn bá tó ǹkan kà lè fọ́àh wá wà níbẹ̀, bí Olódùmarè ṣe fọ́àh sáàrín ilé ayé àtàwọn ayé tókù, àtórìn parú rèé..
wikipedia
yo
Àlàfo tí a ń ṣọ́ yìí, bíi ojú sánmọ̀, ojú òfúrufú ló ṣe rí ṣùgbọ́n nkan tí ó fi yàtọ̀ díẹ̀ ni pé kò sí atẹ́gùn nínú àlàfo yìí, kò sí kùrukùru òfuru jàgédò lásán ni..
wikipedia
yo
Ajá ni wọ́n kọ́kọ́ ran sínú àlàfo tí à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí lọ́dún 1957 láìka lórúkọ tájá yín ń jẹ́, nígbà tájá yí padà tí ó kú ni wọ́n bá rán ẹnìkan ta ń pè ní Yuri gágárin lọ sínú àlàfo yìí, láti orílẹ̀èdè Russia láti mọ Balafo yí ṣe rí Yuri gágárin lẹ́ni àkọ́kọ́ tó kọ́kọ́ fò kúrò lórí ilẹ̀-ayé pátápátá lọ sínú àlàfo ta ń pè ní Space tó wà láàrín ilẹ̀ ayé Asar.
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí orílẹ̀ èdè America náà bẹ̀rẹ̀ sí ní rìnrìnajo yìí ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín Orílẹ̀èdè America lọ sínú òṣùpá lọ́dún 1969 Neil Armstrong àti Edwin AlSarahẹ́múlà sì lẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ wọnú òṣùpá..
wikipedia
yo
Mo sọ fún wa wípé Aláọ́n kan nbẹ nínú ilé ayé tó ma ń fa Ẹrandigó nkan tó bá ti wà lórí ilẹ̀-ayé tàbí súnmọ́ ilé ayé mọ́ra, téèyàn á bá wa kúrò lórí ilẹ̀-ayé pátápátá ẹ̀yán gbọdọ̀ jara rẹ̀ gbà kúrò lọ́wọ́ ọ́nwù yìí, mọ́tò téèyàn a bá lò ó gbọdọ̀ lágbára gidi kò sì tún le sáré láti borí agbára ọ́nwù yìí, tóó ọkọ̀ tí wọ́n gbé lọ inú òṣùpá, kàyín ń jẹ́ o, Aeroplane, ó lè rín irú ìrìnàjò ìrìnàjò yí o, ẹ wòó iṣẹ́ ọ̀pọ̀lọ́ ni wọ́n fi ṣe róréètì yìí, ìpele ni wọ́n ṣe ẹ́ńjìnnì mọ́tò yí o, ìpele kínní, ìpele kejì, ipò kẹta lọ sókè ibi tí àwọn èèyàn dúró sí nùnù rẹ̀, ó wà lórí ìpele kẹta lókè téńté mìíràn Bí wọ́n ṣe tó àwọn ẹ́ńjìnnì yìí bíi àgbà rìbìtì Wọ́n rèé tó dúró lóòró tó wà kojú dá sánmọ̀ wọ́n tún wá jẹ kí ọkọ̀ yìí sẹ́nu ṣọ̀mù ṣọ̀mù kò lè máa wọnú àtẹ̀gùn lọ sọọ́, orúkọ tí wọ́n fún ètò yìí ni wọ́n ń pè ní Apollo 11, Apollo, 11 yìí ga lọ sókè ní ìwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà ọgọ́rùn mẹ́ta ó lé díẹ̀ díẹ̀, bíi ká sọ pé ilé ogójì epo tí ọkọ̀ yìí ń jẹ́ kèrémí kọ ó o..
wikipedia
yo
Bíi ìgbà téèyàn bá yin ọta ìbọn, bí wọ́n ṣe, ma ń yìn-ìn nuu torí ó gbọdọ̀ lè sáré dáadáa kíó lè jára rẹ̀ gba kúrò lọ́wọ́ ọ́nwù tí ń bẹ lórí ilẹ̀ ayé, tí wọ́n á bá sì yín mọ́tò yìí kìí ṣèèyàn kankan ní sàkání ibẹ̀, torí ooru, èéfín àti iná nlọ ma ń jáde ní ìdí rọ́kẹ́ẹ̀tì yìí.Àwọn tó lo inú òṣùpá, tí wọ́n wà nínú mọ́tò yìí..
wikipedia
yo
Wọ́n dẹra wọn mọ́ àga ní àwọn to yín alákòóso yìí sókè, wọ́n jìnnà patapata sí ibi tí ròkètí yìí wà, ẹ̀rọ kọ̀mpútà ni wọ́n fi yìn ín bí wọ́n ṣe gbẹ́nà le alákòóso yìí tí à ń pè ní Apollo 11 ní 1969 dó bá dùn gbọ́a? Lọkọ bá ṣí, ó dókè lójú San mọ́ èrè burúkú kí ọkọ̀ máa sarè ẹgbẹrun mẹ́wàá kìlómítà láàrin wakati kan..
wikipedia
yo
10,000km Irú eré tí àwọn mọ́tò ma ń ṣa lọ́nà ẹṣpù irú eré yìí lọ́nà ẹgbẹ̀rún kan lérè ti rọ́kẹ́ẹ̀tì yìí bá lọ sínú òfúrufú lọ́hùn..
wikipedia
yo
Laarin iṣẹju meji ààbọ̀, ẹ́ńjìnnì tipẹlẹ àkọ́kọ́ ti gbé ọkọ̀ yìí rin kilomita ogorun mefa 600km..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìṣẹ́jú méjì ààbọ̀ ẹ́ńjìnnì tó wà ní ìpele àkọ́kọ́ ti jọ tán ó jábọ́ kúrò lára ọkọ̀ yìí, ẹ́ńjìnnì tí pele kejì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ó sì gbé wọn rin ẹgbẹ̀rún méjì, ó lé ní ọgọrun mẹta kìlómítà 2,300 paradà láàrin ìṣẹ́jú mẹ́fà ló sì nù òfururu lòunlòun, ẹ́ńjìnnì ìpele kejì jọ tán ohun náà jábọ̀, tipẹlẹ kẹ́ta bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ẹ́ńjìnnì tipẹlẹ kẹta ló wà jàwọ́n gbà kúrò lọ́wọ́ ọ́nwù tí ń bẹ nínú ayé pátápátá, wọ́n sì bọ́ sínú àlàfo tí ń bẹ láàrin ilẹ̀-ayé àtoṣù..
wikipedia
yo
Nínú àlàfo yìí, onwù ayé ò ní pa púpọ̀ mọ́ lórí wọn wọ́n wá ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní rìnrìnàjò wọn lọ sínú òṣùpá ní ìrọ̀wọ́ irọ́ṣẹ́..
wikipedia
yo
Nínú àlàfo tí à npè ní Space yìí, béèyàn bá ju nkan òkè kìí padà wá lé yíò dúró pa sókè ni, kò dá gan béèyàn gán fò sókè èèyàn ò ní tètè padà wálé torí kò sí ọ́nwù kan tí ó fàáyàn padà nínú àlàfo yìí ṣùgbọ́n béèyàn bá dénú òṣùpá, ọ́nnu ń bẹ nínú òṣùpá ṣùgbọ́n mé kò tó táyé béèyàn bá ju nkan sókè nínú òṣùpá náà kìí tètè padà wálé, ẹ má gbàgbé àti nínú àfifò tí ń bẹ láàrin ilẹ̀-ayé àtoṣù àti nínú òṣùpá gan-an kò sí atẹ́gùn níbẹ̀ ó báwo wá làwọn tí wọ́n ń lo inú òṣùpá ṣe ma ń mí, wọ́n ma ń gbé àtẹ̀gùn pamọ́ sínú àpò kan ni, kí wọn ó lè rate fi mí..
wikipedia
yo
Toò wọ́n dénú Òṣùpá lógúnjọ oṣù kẹfà lọ́dún 1969 lọ́jọ́ Sunday ọjọ́ ìsinmi ló bọ́ sí ẹ̀yìn tẹẹ̀bá ni kàlẹ́ńdà 1969 lọ́wọ́ ẹ wòó ọjọ́ márùn-ún ni wọ́n fi rin ìrìn ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́rùn mẹ́ta , ó lé ní ọgọ́rùn lọ́nà ogún kìlómítà 320,000km ló sì nu òṣùpá, Neil Armstrong lórúkọ fẹ́ẹ́ ẹni tó kọ́kọ́ fi ẹsẹ̀ tẹnu òṣùpá bó ṣe ń sọ̀kalẹ̀ láti inú ọkọ̀ tí wọ́n gbé lọ òní bí ó ti lé jẹ́pé ìgbésẹ̀ tí òhun gbé wọnú òṣùpá ó kéré òní ìgbésẹ̀ ńlá ni fún ìran ọmọ ènìyàn..
wikipedia
yo
Edwin AlSarahẹ́múlà tí wọ́n dìjọ lọ náà sọ̀kalẹ̀ sínú òṣùpá wọn bá Ààrẹ Orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà nígbànáà ààrẹ Richard nixon sọ̀rọ̀ pẹ́ tó àwọn tí dé sínú òṣùpá o..
wikipedia
yo
Àwọn mejeeji bẹ̀rẹ̀ iwadi tí wọ́n bá lọ sinu òṣùpá wọn fìnọ́ múlẹ̀ pé erùpẹ̀, òkúta àtàwọn òkè ń bẹ ninu òṣùpá ṣugbọn kò sí ẹ̀dá alàyè tabi ohun abẹ̀mí kan níbẹ̀..
wikipedia
yo
Inú òṣùpá tí à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí ọjọ́ méjì tí ẹ oṣù kan ti wà ni ó ṣe méjì gbáko loorun a fi rán..
wikipedia
yo
Tí gbogbo nkan a sì gbọ̀nà lọ́è méjì ju omi tó ń ṣ lọ, òsẹ̀ méjì ní lè tún fi ma ń ṣù, gbogbo nkan a tún tútú lọ́lẹ̀ méjì ju Ice Block lóyin lọ..
wikipedia
yo
Àsìkò ìgbà tóòrùn ń ràn ní wọ́n dé bẹ̀ àmọ́ aṣọ tiwọn wọ̀ dábòbò wọ́n tóoru ó fi mú wọn pa torí wọ́n dọ́gbọ́n ẹ́ńjìnnì Amara tútù sínú aṣọ yìí, àwọn méjèèjì lo wákàtí méjì àtiṣe mẹ́ta dínláàádọ́ta nínú òṣùpá wọn sáwọn ìwàa kèékèé kẹ́ wọn rí àsíá orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà síbẹ̀, wọ́n bu yẹ̀ẹ̀pẹ̀ inú òṣùpá àtòkúta díẹ̀ lọ́wọ́, wọ́n sì padà, tóó àti lọ sínú òṣùpá ló lé àti kúrò níbẹ̀ ó lé, wọ́n yín rà wọ́n kúrò níbẹ̀ ní bí wọ́n ṣe yín rà wọ́n kúrò lórí ilẹ̀ ayé..
wikipedia
yo
Ọjọ́ méjì ààbọ̀ ni wọ́n fi rìn padà sórílẹ̀ ayé bí wọ́n tún ṣe súnmọ́ ilé-ayé Lonfa inú ayé bá tún bẹ̀rẹ̀ sí ní fàwọn, eré ni àwọn sì ń bá bọ̀ láti inú òṣùpá tẹ́lẹ̀ lérè yìí bá tún pọ̀ sí, báwo lọkọ ṣe fẹ́ bà sórí ilẹ̀ pẹ̀lú eré burúkú yìí Iap,” ọtí wo ló fẹ́ bá sí wọn sá ṣètò kí mọ́tò yí balẹ̀ sínú òkun alagbalúgbú omi See Mo pe òkun jìn lọ ìsàlẹ̀, omi inú òkun tún dá mọ́tọ̀ yìí dúró bíi burékì, toô bí wọ́n ṣe lọ sínú òṣùpá rèé ó..
wikipedia
yo
Lọ́jọ́ kẹrìndínlógún oṣù keje ọdún 1969 16-7-1969 tí wọ́n sì padà sórí ilẹ̀ ayé lọ́jọ́ kẹrìnlélógún, oṣù keje kannáà lọ́dún 1969, 24-7-1969.
wikipedia
yo
Baṣọ̀run Gáà jẹ́ ìwé ìtàn eré-oníṣe ti gbájúmọ́ òǹkọ̀wé ni, Adébáyọ̀ Fálétí kọ..
wikipedia
yo
Ó dá lórí ìtàn olóyè Baṣọ̀run ti ìlú Ọ̀yọ́ ti wọ́n ń pè ni Baṣọ̀run Gáà..
wikipedia
yo
Kókó inú Iwe Ìtàn eré oníṣe yìí ni wípé kí a má ṣe ìkà..
wikipedia
yo
Ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá ni òǹkọ̀wé náà fi kọ ìwé náà, tí ó sì gbé ìtàn rẹ̀ lé orí ìtàn gidi tí ó sì jẹ́ ojúlówó ìtàn ilẹ̀ Yorùbá.Ìtàn ìgbésíayé Baṣọ̀run Gáà bí àkọsílẹ̀ kan ni BBC, ìtàn fi yé wa pé, Baṣọ̀run Gáà ni olórí ìgbìmọ̀ Ọ̀yọ́mèsì, èyí tó dàbí olóòtú ìjọba láyé òde òní, lẹ́yìn Aláàfin, tíí ṣe Oriade ìlú Ọ̀yọ́, Baṣọ̀run Gáà ló tún kú.Kò sí seni tó le è sọ pé tí Baṣọ̀run kọ́gàá kò jẹ́ èèyàn gidi, wọ́n yóò fi jẹ oyè Baṣọ̀run, tó jẹ́ olórí Ìgbìmọ̀ Ìwé-Osa fún Aláàfin, tíí ṣe Ọ̀yọ́mèsì. Ní báyìí, ó wá yé mọ́ ìtàn ìgbé gíga akọni yìí àti ipa tó kó ni ìlù rẹ̀, bóyá rere ni Àbí búburú. Ggíga ni olórí ogun Ọ̀yọ́ ilẹ̀ àti gbajúmọ̀ ìlú ni sáà ka ẹgbẹ̀rún ọdún kẹtàdínlógún sí ìkejì lógún, 17th/ Century d ṣe gudugudu méje àti ya a ya mẹ́fà láti ríi dájú pé Ọ̀yọ́ ilẹ̀ àkọ́kọ́ di ìlú ńlá, ó lágbára, tó sì fẹ́ dé ọ̀pọ̀ ìlù àti orílẹ̀-èdè lóde òní nígbà 1750 ni Aláàfin sì yan Glí gẹ́gẹ́ bíi Baṣọ̀run, olóòtú àti olórí Ìgbìmọ̀ Ìgbìmọ̀ Ìwé Ẹmíràn méje fún Aláàfin Ọ̀yọ́ ilẹ̀ ilẹ̀, tí agbára sì ń pa G
wikipedia
yo
Nàìjíríà ránka jẹ́ orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà (Nigeria ní èdè Gẹ̀ẹ́sì) jẹ́ orílẹ̀-èdè ìjọba àpapọ̀ Olómìnira tí ó ní ìjọba ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tó fi mọ́ agbègbè oluilu ìjọba àpapọ̀..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wà ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Áfríkà..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè yí pààlà pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Benin ní apá ìwọ̀ oòrùn, ó tún pààlà pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Olómìnira ti Nìjẹ̀r ní apá àríwá, Chad àti Kammetá ní apá Ìlà Oòrùn àti Okun Atlantiki ní apá gúúsù..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Nàìjíríà ni ẹ̀yà púpọ̀, àwọn ẹ̀yà mẹ́ta ni wọ́n hànde tí wọ́n tóbi jùlọ, tí wọ́n sì pọ̀ jùlọ, tí a sì kọ́ àwọn ẹ̀ka ìsọ̀rí ìsọ̀rí ẹ̀yà tókù sí abẹ́ wọn..
wikipedia
yo
orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ìtàn fífẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹ̀rí ìmọ̀-àìjọ́un fihàn pé àwọn ìgbẹ́ ènìyàn ní agbègbè ibẹ̀ ló sẹ́yìn dé kéré pátápátá ọdún 9000 kj..
wikipedia
yo
Agbegbe Benue-Cross River jẹ rírọ gẹgẹ bi ilẹ akọkọ awọn Bantu àròkere ti wọn fan kaakiri opo aarin ati apaguusu Afrika bi iru omi ni aarin Ẹgbẹ̀rúndún akoko ati Ẹgbẹ̀rúndún Keji..
wikipedia
yo
Orúkọ Nàìjíríà wá láti odò ọya, ti a tún mọ gẹ́gẹ́ bíi odò Nàìjá, èyí tó sàn gba Nàìjíríà kọjá..
wikipedia
yo
Flora Shaw, tí yio jẹ́ ìyàwó lọ́jọ́ wájú fún Baron Lugard ara Britan tó jẹ́ alámójútó àmúsìn, ló ṣẹ̀dá orúkọ yìí ní òpin ọdún 1897.Nàìjíríà ní orílẹ̀-èdè tó ní èèyàn púpọ̀ jùlọ ní ilẹ̀ Aláwọdúdú, ìkẹjọ ní àgbáyé, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ orílẹ̀-èdè tó ní àwọn ènìyàn aláwọ̀dúdú jùlọ láyé..
wikipedia
yo
Ó wà lára àwọn orílẹ̀-èdè tí à ń pè ní “Next Eleven” nítorí okòwò wọn, ó sì tún jẹ́ ọ̀kan nínú àjọní àwọn ibi..
wikipedia
yo
Okòwò ilẹ̀ Nàìjíríà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn èyí tó ń dàgbà kíákíá jùlọ lágbàáyé pẹ̀lú IMF tó ń gbèrò ìdàgbàsókè 9% fún 2008 àti 8.3% fún 2009..
wikipedia
yo
Ni ibere awon odun 2000 soke, ogun awon omo Naijiria gbe pelu iye to din ni US$ 1.25 (PPP) pamo..
wikipedia
yo
Nàìjíríà ni okòwò rẹ̀ tóbi jùlọ ní Áfíríkà, àti alágbára ní agbègbè ìwọ̀òrùn Áfíríkà.Tan ìsẹ̀ǹbáyé àwọn ará NOK ní àárín Nàìjíríà ṣe eré gbígbẹ́ alámọ̀ tí àwọn onímọ̀ ayéejòràn ti wárí..
wikipedia
yo
Eré NOK tó wà ni Minneapolis Institute of Arts, Jùwé ẹ̀ ẹni pàtàkì kan mú “ọ̀pá ìdaran” dáni ní ọwọ́ ọ̀tún àti igi ní ọwọ́ òsì..
wikipedia
yo
Ìwọ̀nyí ni àmì-ìdámọ̀ aláṣẹ tó jẹ́ bíbápọ̀ mọ́ àwọn Farao ilé Egypti ayéejòun àti òrìṣà, Osiris, èyí ló ń sọ pé irú àwùjọ, ìdímúlẹ̀, bóyá àti ẹ̀sìn ilẹ̀ Egypti ayéijọ́un wà ní agbègbè ibi tí Nàìjíríà wà lónìí ní ìgbà àwọn Farao..
wikipedia
yo
Ní apá àríwá, Kano àti ìṣàkóso ní ìtàn àkọsílẹ̀ tí ọjọ́ wọn dẹ̀yìn tó bí ọdún bẹ̃ge K..
wikipedia
yo
Awon ilu-oba Hausa ati ile-ọba kanem-Bornu gbooro gege bi ibudo aje laarin ariwa ati ìwọ̀oòrùn Afrika..
wikipedia
yo
Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rúndún 19sá lábẹ́ Usman Dan fodio àwọn ará Fulani di àwọn olórí ilẹ̀-ọba Fulani Lójúkan èyí tó dúró bayi títí di 1903 nígbàtí wọ́n jẹ́ pínpín láàrín àwọn Ibikàsin ará Europe..
wikipedia
yo
Láàrín 1750 àti 1900, ìdá kan sí ìdá méjì nínú mẹ́ta àwọn oníbùgbé àwọn ìlú Fúlàní jẹ́ ẹrú nítorí ogún.Àwọn Yorùbá ka ọjọ́ tí wọ́n ti wà ní agbègbè Nàìjíríà, Benin àti Togo ayéòdeòní sẹ́yìn dé bí ọdún 8500 Kj..
wikipedia
yo
Àwọn ìlú-ọba Ifẹ̀ àti Ọ̀yọ́ ní apá ìwọ̀òrùn Nàìjíríà gbalẹ̀ ní 700-900 àti 1400 ní ṣíṣẹ̀ntẹ̀lẹ̀..
wikipedia
yo
Síbẹ̀síbẹ̀, ìtàn Arisọ Yorùbá gbàgbọ́ pé Ilé-Ifẹ̀ ni orisun ẹ̀dá ènìyàn pé bẹ́ẹ̀ si ni ó ṣíwájú Àṣà-Ọ̀làjú mìíràn..
wikipedia
yo
ÌFẸ́ ṣẹ̀sọ eré alamọ àti oníganran, Ilu-ọba Oyo si fẹ́ de ibi ti Togo wa loni..
wikipedia
yo
Ìlú-ọba mìíràn tó tún gbálẹ̀ ni gúúsù apáìwọ̀òrùn Nàìjíríà ni Ìlú-Ọba Benin láti ọ̀runbí 15 19SA..
wikipedia
yo
Ijoba won de ilu Eko ki awon ara Portugal o to wa so ibe di "Lagos.”Ni apa guusu ila-oorun Naijiria, ilu-ọba nri ti awon Igbo gbooro laarin laarin orundun 10wa titi de 1911..
wikipedia
yo
nri ati Agulérí, nibi ti itan ariso ida Igbo ti bẹrẹ, wa ni agbegbe iran UErieri, awon ti won so pe iran awon de ile-ọba eri funra re.Igba àmúsìn awon Portuguese Empire ni won je ara Europe akoko to bere bere isowo ni Naijiria ti won si so ebute Eko di Lagos ti won mu lowolowo oruko ilu Lagos ni AlGarve..
wikipedia
yo
Orúkọ yìí lè mọ́bẹ̀ bí àwọn ará Europe mìíràn náà ṣe bẹ̀rẹ̀ síni ṣòwò níbẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ará Europe ṣòwò pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà abínibí ní ẹ̀bá-odò, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ òwò ẹrú níbẹ̀, èyí tó pa ọ̀pọ̀ àwọn ẹ̀yà abínibí Nàìjíríà lára..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ogun Napoleon bẹ̀rẹ̀, àwọn ará Britani fẹ́ ìṣòwò dé àárín Nàìjíríà..
wikipedia
yo