cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Nínú ìbáṣepọ̀ wọn, àwọn ọ̀rọ̀ náà ń ṣiṣẹ́ lórí ara wọn tó fi jẹ́ pé àwọn òwò kan a gba àwọn mìíràn yóò sì fún wọn ní àwọn àbùdá kan..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ orúkọ náà, tó máa ń jẹ́ olùkópa, kìí ṣe òṣèré tàbí àkọ́so tí ọ̀rọ̀ kò bá fún wọn ní irú ipa bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Nínú ọ̀rọ̀ - èdè ti ayé (tí a gbé wọnú gírámà) ọ̀rọ̀ ìṣe tó ń darí abo apór rẹ̀ fún ìdí èyí, ó ń fún ní ìṣe (ní báyìí, ó rọlẹ̀ nìkan, àmọ́ ó lè ṣe àyànṣe àwọn àwomọ mìíràn).Gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́ èdè ṣe nu ìmọ̀ nípa àwọn nǹkan wọ̀nyí láìkò tí ó sì jẹ́ pé dandan ni ó ń tẹ̀lé àwọn òfin yìí, ṣé a kò lè sọ pé àwọn ọgbọ́n ẹ̀tọ́ yìí jẹ́ abínibí gẹ́gẹ́ bí mímí ṣe jẹ́? 2.4Àwọn ibi gíga ìwọ̀n mìíràn ni a ti mẹ́nu bà tẹ́lẹ̀, nípa ọ̀rọ̀ náà, ohùn náà ni pé kìí jẹyọ ní dídáwà..
wikipedia
yo
Ọ̀lẹ di ọ̀lẹ̀ náà, ògbójú ọ̀lẹ náà, ògbójú alágbára ọ̀lẹ náà pẹ̀lú ìwọ, abbl..
wikipedia
yo
Àwọn ìpọ̀pọ̀ ọ̀pọ̀ náà sí àwọn owó tí ó tóbi pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn ohun tí a pè ní àwọn àpólà..
wikipedia
yo
Nítorí pé àárín ọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ gangan tí a bá túnṣe ni yóò dúró fún odidi àpólà, a máa ń pe ìrù wọn ní orí..
wikipedia
yo
Ní a ṣe maa rí i, ọ̀rọ̀ orúkọ ni ó maa ń jẹ́ orí fún àpólà orúkọ (àpór), ọ̀rọ̀ iṣẹ́ fún àpólà iṣẹ́ (apènìyàns), ọ̀rọ̀ tàbí fún àpólà àpèjúwe (apá). ìdá tàbí Y tún àpólà x (x) àti àpólà y (pp) bákan náà.lẹ́ẹ̀kan si, ka wò ó pé Olùgbé ẹ̀ka -èdè rẹ̀ mọ́ púpọ̀ nípa rẹ̀..
wikipedia
yo
Yorùbá máà mọ mo pé ọmọ ‘Child’ ni a lè to àwọn ọ̀rọ̀ ẹ̀pọ́n mọ bí i ọmọ kékeré ‘Small Child', Ọmọ Baba Ìbàdàn ‘The Child of the man from Ìbàdàn’ tàbí ọmọ náà “The Child” di di dandan, àti pé kódà, wọn kò tí ì kọ́ ní àwọn àtòpọ̀ yìí rí..
wikipedia
yo
Ati wí pé ọ̀pọ̀lọ́ tí olùṣọ́ ẹ̀ka-èdè yìí ń lọ ni a fẹ́ gbéyẹ̀wò ninu girama, akitiyan lati mọ ohun ti o mọ̀ lai kọ..
wikipedia
yo
ṣé kò pani lẹ́rìn-ín, olùṣọ́ ẹ̀ka - èdè, tàbí ọmọdé kan ń kó àwọn òrimọ́ ẹ̀dá-èdè kò ní ìtumọ̀ ṣùgbọ́n òótọ́ ni.A ṣe àfiikùn àwọn àpólà tí a kò tí olùṣọ́ ẹ̀ka-èdè lè lọ pé kò ní ẹkùn ó sí peléke..
wikipedia
yo
Àwọn ìní ìhun bẹ́ẹ̀ lè kún fún àwọn èròjà wòfún tí ó wọnú ara wọn..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n èyí kéyìí tó bá ṣẹlẹ̀, àpólà gbọdọ̀ ní orí, títẹ̀lé àwọn ohun tí òfin níní orí gbà, tí a pè ní ‘Enaniri wQnmìMrnt
wikipedia
yo
Nítorí bẹ́ẹ̀tí a bá ní ọ̀rọ̀ kan w, ó gbọ́dọ̀ di w Max tí a túpalẹ̀ ní síntáàsì gẹ́gẹ́ bí i WP (for W-phrase) tàbí W" (W- double Prime (Barbar)sáyẹ́ǹsì). Kọ̀m̀pútà..
wikipedia
yo
OLábánì James Aahiẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀ nipa ìfitónilétí (inforHealth)Èkó ijinlẹ nipa ìfitónilétí n kọ nipa ẹ̀tọ́, ìṣesí àti ìbáṣepọ̀ àwọn ìlànà àdánidá àti ìfi-i-ṣe, tó ń pamọ́, tó si ń ṣe ìyípadà àti ìkójọ ìfitónilétí..
wikipedia
yo
Bákan náà, ni ó ń ṣẹ̀dá àwọn ìpínlẹ̀ Ajémèrò àti tíọ́rì tirẹ̀..
wikipedia
yo
Ni ode-oni, "informatik" ni won n lo dipo "computerwissestàbí ni orile-ede Germany eyi to tumọ si (computer Science) ni ede Geesi, ti o si tumọ si imo ijinle nipa ero koKọmputa ni won ti soro nipa eko ijinle nipa ìfitónilétí..
wikipedia
yo
Bákan náà oríṣìíríṣìí àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ẹ̀rọ kọ̀mpútà láti àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé ni ó fún ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀ nípa ìfitónilétí ní oríkì tiwọn pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Ikini ni pe iyipada to ba imọ, ijinle ìfitónilétí ni won ti yọ kuro, gege bi ti Eko Ìyìnle nipa Ifito to jẹmọ́ eto Oro-aje ati Ofin ikeji ni, nigba ti o je pe opo ninu awon ìfitónilétí yii ni won ti n ko pamo Àjàpá tòde-oni, idiyele ti wa je pataki si Eko ijinle nipa ìfitónilétí orile je ilo ati ibanisoro nipa ìfitónilétí ti a ro po lati lo fun iwadii, nigba ti o je pe won ti gba won gege bi ohun to se pataki si ohun kóhun to ba je imo ijinle.Fun idi eyi ni gbogbo awon orile-ede ti o ti goke agba ni agbaye, won ko fowo yẹpẹrẹ mu eko ijinle nipa ìfitónilétí ati gbogbo ohun to so mo o sayensi lori Kọmputa..
wikipedia
yo
ṣaláìlera ìdáyáyá Olúwafìmọ̀ ẹ̀rọbí a bá n sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ bí akọ bá sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ sáyẹ́ńsì, a jẹ́ pé à ń rọlẹ̀ apá kan nìyẹn..
wikipedia
yo
Báwo ni a ó ò ṣe pe orí ajá tí a kò níí pe orí ìkọ̀kọ̀ tí a fi ṣe é? Ìmọ̀ ṣàyàn ló bí ìmọ̀ ẹ̀rọ..
wikipedia
yo
ṣàyànsì ni yóò pèsè irinṣẹ́ tí ìmọ̀ ẹ̀rọ máa lò láti fi ṣe agbára..
wikipedia
yo
Ọ̀nà meji ló yẹ kí á gbé àlàyé wa kà nígbà tí bá ń sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ..
wikipedia
yo
(1)Ìmọ̀ ẹ̀rọ àbáláyé (ANIci Technology) (2)Ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé (Modern Technology) ìmọ̀ ẹ̀rọ àbáláyé ní ìgbà àwọn baba ńlá wa, tí ojú sì wá lórúnkún, ọ̀nà láti wá ojútùú sí ìṣòro tó wà láwùjọ bóyá nípa ilé gbígbé, aṣọ wíwọ̀ oúnjẹ jíjẹ ló fà á tí àwọn baba ńlá wa fi máa ń lo ìmọ̀ sáyẹ́ńsì tiwantiwa láti sẹ́dàá àwọn nǹkan àmúṣagbára lásìkò náà..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ nínú àwọn ìmọ̀ èrò ìgbà náà ló di iṣẹ́ ó ọjọ́ tí àwọn baba ńlá wa ń ṣe lásìkò náà..
wikipedia
yo
Wọn a tún máa sọ pé bí oúnjẹ bá kúrò ninu ìṣẹ́, iṣẹ́ bùṣe”
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí wọ́n fi wá ohun èlò láti máa ṣe àwọn iṣẹ́ òòjọ́ wọn bí iṣẹ́ àgbẹ̀.Iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ ilẹ̀ wa..
wikipedia
yo
Àwọn baba ńlá wa máa ń lo oríṣìíríṣìí irin iṣẹ́ láti wá ohun jíjẹ lára wọn ní àdá, ọkọ́, àgbọn, akọ́rọ́ ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ àgbẹ̀ gan an ni ojúlówó iṣẹ́ nígbà náà lára àwọn irin-iṣẹ́ tí àwọn ọdẹ máa ń lò ni, ọkọ́, àdá, ìbọn, òògùn àti àwọn yòókù..
wikipedia
yo
Nígbà tí a bá jẹun yó tán, nǹkan tó kù láti ronú nípa rẹ̀ ni bí a óo ṣe bó ìhòhò ara..
wikipedia
yo
Èyí ló fà á tí àwọn baba ńlá wa fi dọ́gbọ́n aṣọ híhun..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, àwọ̀ ẹran ni wọ́n ń dà bora lákòókò náà, ṣùgbọ́n wọ́n ní ọ̀kánjúà ń dàgbà ọgbọ́n ń rewájú ọgbọ́n tó rewájú lọ fàá tí àwọn èèyàn fi dogbọ́ aṣọ híhun lára òwú lóko..
wikipedia
yo
Láti ara aṣọ òfì, kíjìpá àti sányán ni aṣọ ìgbàlódé ti bẹ̀rẹ̀ ilẹ̀ gbígbẹ..
wikipedia
yo
Bí a bá bo àṣírí ara tán ó yẹ kí á rántí ibi fẹ̀yìn lélẹ̀ sí..
wikipedia
yo
Inú ihò (CARA) la gbọ́ pé àwọn ẹni àárọ̀ ń fi orí pamọ́ sí i ṣùgbọ́n bí ìdàgbà sókè ṣe bẹ̀rẹ̀, ni àwọn èèyàn ń dá ọgbọ́n láti ara ìmọ̀ ọ̀pẹ, koríko àti ewéko láti fi kọ́ ilẹ̀..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ aró (alágbẹ̀dẹ)Bi a bá n sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ láwùjọ Yorùbá bi a kò mẹ́nu ba iṣẹ́ alágbẹ̀dẹ, a jẹ́ pé àlàyé wa kò kún tó..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ Aró Túmọ̀ Sí Kí A Ro Nǹkan Tuntun jáde fún Ìwúlò Ara Wa..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ nínú irinṣẹ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ tí àwọn àgbẹ̀ nlò ló jẹ́ pé àwọn alágbẹ̀dẹ ló máa ń ṣe é..
wikipedia
yo
Irinṣẹ́ àwọn ọ̀mọ̀lé, ahunṣọ, àwọn alágbẹ̀dẹ ni yóo rọati jáde..
wikipedia
yo
Irinṣẹ́ àwọn ọdẹ, àwọn ọ̀mọ̀lé àwọn alágbẹ̀dẹ ló ń rọ gbogbo rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìmọ̀ ẹ̀rọ gan-an lọ́dọ̀ àwọn alágbẹ̀dẹ ló ti bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
Tí a bá ṣe àtúpalẹ̀ èrò yóò fún wa ní ẹ̀ -mọ́fíìmù àfòmọ́ ìbẹ̀rẹ̀ ro –ọ̀rọ̀-ìṣe adádúró ẹ̀ +rọ̀ díẹ̀oṣù > ero..
wikipedia
yo
Rírọ́ nǹkan ntún jáde ní èrò ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì gẹ́gẹ́ bí ń ṣe sọ ṣáájú lọ bí ìmọ̀ ẹ̀rọ..
wikipedia
yo
Ó yẹ kí á fi kún un pé, ọpọ́n ìmọ̀ ẹ̀rọ ti sún síwájú báyìí..
wikipedia
yo
Ìdí èyí ni pé ìmọ̀ ẹ̀rọ tó ti ọ̀dọ̀ àwọn òyìnbó aláwọ̀ funfun wá ti gbálẹ̀gbóko..
wikipedia
yo
Àwọn ọ̀nà tí à ń gbà pèsè nǹkan rírò ti yàtọ̀ báyìí..
wikipedia
yo
Ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé lẹ́yìn ìgbà tí ọ̀làjú wọ agbo ilé Yorùbá ni ọ̀nà tí à ń gbà ṣe nǹkan tó yàtọ̀..
wikipedia
yo
Ṣugbọn ó yẹ kí á ranti pé kí àgbàdo tóó dáyé ohun kan ni adìyẹ ń jẹ..
wikipedia
yo
Àwọn nǹkan tí adìẹ́ ń jẹ náà láti ṣàlàyé ninu ìmọ̀ ẹ̀rọ àbáláyé..
wikipedia
yo
Ẹ jẹ́ kí a wo ilé kíkọ́ àwọn ohun èlò ìgbàlódé ti wà tí a lè fi kọ́ ilé alájàmẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Ìmọ̀ ẹ̀rọ náà ló fàá tí àwọn mọ́tò ayọ́kẹ́lẹ́ fi dáyé..
wikipedia
yo
Ero mohunmaworan, asọ̀rọ̀, Ero ti n fẹ atẹ́gùn (fan), ero to n fẹ tutu fẹ gbígbóná (Air condition) apẹẹrẹ mìíràn ni ero ibanisoro, alagbeeka, ero komputa, ero alukaleluko (Internet)..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn àpẹẹrẹ yìí ni ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé tií máyé dẹrùn fún mùtúmùwà..
wikipedia
yo
Àwọn àléébù tí wọ́n náà wà, ṣùgbọ́n iṣẹ́ àti ìwúlò wọn kò kéré rárá...
wikipedia
yo
Odùduwà jẹ́ aláṣe àti olùdarí ìran Yorùbá, òun tún ni gbòngbò kan pàtàkì tí ó so ilẹ̀ Yorùbá rọ̀ láti Ifẹ̀, títí dé ibi k'ibi tí wọ́n bá ti ń jẹ Ọba kirikirikiri ilẹ̀ Kkó –ọ -jíire pátá..
wikipedia
yo
Lára ìtàn tó fẹsẹ̀ Odùduwà múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọni ìgbà ìwáṣẹ̀ nílẹ̀ Yorùbá sọ wípé ó jẹ́ ọmọ ọba ti ilẹ̀ Lárúbáwá tí wọ́n f'ógun lé kúrò nílùú bàbá rẹ̀ nílẹ̀ Mẹ́kà tí ó wá di Saudi Arabia lónìí..
wikipedia
yo
Látàrí ogun yìí ló jẹ́ kí ó gbéra òun àti àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ tí wọ́n sì fi tẹ̀dó sí ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà títí di òní..
wikipedia
yo
Tuse sí ohun kan tí ó dá ohun tó ṣeé foju rí.Nigba tí ó ku díè kí Odùduwà ó kúrò lálaye, ọ̀pọ̀ àwọn ọmọìròyìn ni wọ́n tinfún ká orílè kúrò ní ìfẹ́, tí wọ́n sísí Kailà -laaka kãkiri ní àwọn náà..
wikipedia
yo
Ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ni wọ́n ti dá ìjọba tiwọn náà kalẹ̀ nílú tí àwọn náàbtẹ̀dó sí Gẹ́gẹ́ bí ọba, tí wọ́n sì ń fi yé àwọn ọmọ tiwọn náà wípé Ilé-Ifẹ̀ ni àwọn tí Warúnrún tí ó jẹ́ ọmọ tí ọ̀kan lára àwọn erú Odùduwà bí fún ni ó jẹ́ ìyá-ńlá àwọn tí wọ́n ń joyè Ọbalúfe tí ó jẹ́ oyè igbá-kejì sí oyè Ọọ̀ni ní Ilé-Ifẹ̀ títí dòní Ọbalúfọ̀n àlàyémore ni ó wà ní orí Ire nígbà tí Ọ̀rànmíyàn ti ìrìn-àjò dé, tí ó sì pàṣẹ pé kí Ọbalùfọ̀n ó kúrò lórí àpèrè kí óhn sì bọ́ síbẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ọmọ Odùduwà tí ó lẹ́tọ̀ọ́ yẹ̀yé bàbá rẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn lajájà tí ó jẹ́ ọmọ Ọ̀rànmíyàn bí ó ni àwọn ọmọ rẹ̀ ń jẹ́ Ọọ̀ni nílé-Ifẹ̀ títí dòní.Lápá kan, wọ́n ní ìtàn Fiyèni wípé Odùduwà jẹ́ oníṣẹ́ láti ìlú Òkè-ọrá ìlú tí ó wà ní apá ìlà -Oòrùn ẹ̀-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Abala ìtàn yí fi yéwa wípé jagun jagun ni Odùduwà jẹ́ pẹ̀lú bí ó ṣe wọ̀ éwù ogun onírin .Lásìkò tí ó wọ Ilé-Ifẹ̀ wá, àjọṣepọ̀ tó lọ́ọ̀rìn wà láàrín àwọn olùgbé ìran mẹ́tàlá(13) Ifẹ̀, tí ìlú kọ́ọ̀kan sì ní Ọba tirẹ̀ bí Ọba Ìjùgbé, Ìwínrín, Ijió, Ìwínrín àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Lẹ́yìn tí Odùduwà di aláṣẹ Ilé-Ifẹ̀ tán, Òun àti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ sapá tí wọ́n sì gba àwọn ìlú àti agbègbè mẹ́tàlá tí a mẹ́nu bà wọ̀nyí, tí wọ́n sì ṣí sí Ọbàtálá, nípò gẹ́gẹ́ bí olórí tí wọ́n sì gbé ìjọba titun titun pẹ̀lú ètò ìṣèlú tó fẹsẹ̀ múlẹ̀..
wikipedia
yo
Látàrí ìdí èyí, ni wọ́n fi n pèé ní Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀ àkọ́kọ́ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó mú ètò àti ìlànà ìṣèjọba aládé wọ̀ ilẹ̀Yorùbáiran Òwu gẹ́gẹ́ bí ọmọ Odùduwà àkọ́bí Odùduwà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ọ̀kanbí iyùnadé, ni ó fẹ́ Ọbàtálá tí ó sì bí ẹbí tí ó jẹ́ Olówu àkọ́kọ́..
wikipedia
yo
Ìtàn fiblélẹ̀ wì Olówu àkọ́kọ́ yìí ni ó ti gorí ìtẹ́ látìgbà tí ó ti wàní òpóǹkú.Ìran Aláké gẹ́gẹ́ bí ọmọ Odùduwà ọ̀kan lára àwọn ìyàwó Odùduwà tí ó jẹ́ ààyò tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ọmọnídè, ni ó bí Sopasan, ẹni tí ó bí ọba Aláké Sopasan was the first to leave Ilé-Ifẹ̀ with his mother and crown..
wikipedia
yo
He settled at such alẹ́láìsí sites as oke-ọyàn and aro..
wikipedia
yo
The migrants stayed for a number of bóyá and broke Camp in the reign of the Seventh King, Ede, who revived the westward migrations and founded a dynasty at Ketu.Odùduwà and the line of Ọ̀ràngún ajagunla fàgbàmila Ọ̀ràngún, tí a lè pè ní ojúlówó ọmọ Odùduwà ní ó jẹ́ Ọ̀ràngún ilé Ile-Ìlála..
wikipedia
yo
Odùduwà ni a gbọ́ wípé ó fẹ́ láti bí ọmọ yanturu kí ó lè dẹ́kun àhesọ nípa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìfà oracle, he went to a stream, where he found a ńjẹlé Lady by the name of Adetìn Anasìn..
wikipedia
yo
She eventually became his wife and the mother of Ifagbamila (which means "ifá saves me")onitálákà gẹ́gẹ́ bí ọmọ Odùduwà àwọn àrọ́mọdọ́mọ onínísà ni ó ń jẹ ọba Nànísà títí dòní.Onípópó gẹ́gẹ́ bí ọmọ Odùduwà Abiketa ọmọ onípópó ni wọ́n jọba pópó dórú Aláàfin Èfín Ẹ̀ro bí ọmọ Odùduwà Ọ̀rànmíyàn ni ó tẹ ìlú Oyo-ilẹ̀ dó-ilẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí lára àwọn ọmọ rẹ̀ Àjàká àti Ṣàngó náà darí ìjọba Ọ̀yọ́ lẹ́yìn baba wọn.Ọ̀rànmíyàn Ọ̀rànmíyàn tí ó jẹ́ àbíkẹ́yìn àwọn ọmọ Odùduwà ni onírìn-àjò jùlọ láàrí àwọn ọmọ bàbá rẹ̀ jùlọ..
wikipedia
yo
Òní ẹni àkọ́kọ́ tó kọ́kọ́ jẹ hé was the first ọba ilẹ̀ Ìbìní tí ó sì tún jẹ́ ỌbaAláàfin ti ìlú Ọ̀yọ́, bákan náàni òun ni ọba Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀ ẹlẹ́kẹfà nínú ètò.Mọ́remí àti àwọn Ùgbò lẹ́yìn tí àwọmọ Odùduwà gbogbo ti túká kúrò ní Ifẹ̀ láti lọ dá ìlú àti ìletò tiwọn sílẹ̀, ó ṣòro láti tukọ̀ ìlú náà fún olórí tó wà níbẹ̀ nígbà náà, fúndìí èyí, àwọn ìpèníjà oríṣiríṣi ní ó dojú kọ Ilé-Ifẹ̀ lásìkò yí..
wikipedia
yo
Àwọn ẹmẹ̀wà Ọbàtálá tí ó jẹ́ ẹni tó ti darí Ifẹ̀ ṣáájú Odùduwà ni a gbọ́ wíọé wọ́n sọra wọn di agbọ̀n onígàn oró tí wọ́n sì ń gbẹẹ̀mí àwọn ènìyàn lọ́nà àìtọ́, léte àti gbẹ̀san gbígba agbára tí Odùduwà gba agbára lọ́wọ́ Obàtálá..
wikipedia
yo
Wọn yóò múra gẹ́gẹ́ bí Th àlùjọ̀nú nígbà tí wọn yóò wọ àwọn kankankan tó dàbí ewé, lọ́nà tí hòo dẹ́rù ba àwọn ènìyàn gidigidi, wọn yóò ma dáná sunlé tí wọn yóò ja àwọn ọlọ́jà lólè láàrín ọjà..
wikipedia
yo
Lásìkò yí ni ọmọba bìnrin Mọ́remí Ajasoro, tí ó jẹ́ ọmọba bìnrin ní ìlú Ọ̀fà, tí ó wá láti ìran Ọlábà Ọlọ́fà gangan, tí ó jẹ́ ẹni tí ó tẹ ìlú Ọ̀fà dó tí ó sìb jẹ́ adarí pàtàkì fún Ìní Nía ní ìlú Ọ̀yọ́, tí ó sì tún jẹ́ ìbátan Ọ̀rànmíyàn ni a gbọ́ wílé ó dá sí ìṣẹ̀lẹ̀ náà tí ó sì sapá gidi láti pẹ̀tù sí wàhálà náà níoa ṣíṣe alámí àwọn níṣẹ́ búburú náà..
wikipedia
yo
ó fara rẹ̀ sílẹ̀ láti jẹ́ kí wọ́n fipá kó ọpọ lẹ́rú..
wikipedia
yo
Nínú ìgbèkùn ẹrú rẹ̀ ni Ọba àwọn Ùgbò náà ti fẹ láti fi ṣaya..
wikipedia
yo
Àmọ̀ náà gbìyànjú lati bá múfẹ̀ẹ́ lẹ́yìn tí ó fẹ́ Yagba ṣùgbọ́n Mọ́remí kọ́ jale ní tori ó ti ìyẹ orí tẹ́lẹ̀, àti wípé iṣẹ́ alaè lọ wá ṣe kìí ṣe ọ̀rọ̀ ìfẹ́ lọ kan..
wikipedia
yo
Ó ní bí Ọba náà bá le dọ ìdí abájọ àwọn amòòkùn-ṣìkà náà fún òun, kíá ni òun yóò gbà fun lát lájọpọ̀..
wikipedia
yo
Ọba náà kọọ́ jálẹ̀ láti ṣe èyí, ṣùgbọ́n ó ṣe ìfẹ́ inú Morèmi tí ó sì tú àṣírí náà sí lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Ó sọ fún Mọ́remí wí wípé ohun tí àwọn kórìíra jùlọ nígbà tí àwọn bá ti múra bí àlùjọ̀nnú náà bí iná, nítorí iná nìkan ló lè tú wọ́n láṣìí, bí wọ́n bá sì ríná, àwọn yóó sá lọ..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí Mọ́remí ti gg àṣírí yìí tán ni ó bẹ̀rẹ̀ sí ń dọ́gbọ́n ọ̀nà tí yóò gbà sákúró níbẹ̀..
wikipedia
yo
ònó ní kí wọ́n bá òun wá ọsàn tó pọ̀ tí ó sì fi ṣe òògùn ọrun fún gbogbo àwọn olùgbé ààfin náà..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí wọ́n jí ni wọ́n rí wípé mọ́mímí ti na pápá bora tí ó sì ti lọ tú àṣírí àwọn fún àwọn ènìyàn rẹ̀,..
wikipedia
yo
Báyìí ni àwọn Ifẹ̀ ṣe múra sílẹ̀ fún àÙgbo la ti bá wọn bami ìjà wò..
wikipedia
yo
Tí wọ́n sí ṣẹgun wọn.Awon oníwòwò mìíràn nípa Oduwàipa tí Odùduwà kó nínú ìṣẹ̀dáyé awọ ìtàn ibile kam di mule wípé Odùduqq jẹ́ ọkàn lára àwọn orisa tí Elédùmarè de jùlọ nígbà ìwáṣẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ìtàn wọ̀yí fi múlẹ̀ wípé Odùduwà ni Elédùmarè rán wá sáyé láti pólórí ayé sórí ẹ̀kún omi..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ yìí ni a gbọ́ wípé Ọbàtálá kùnà láti jẹ́ lẹ́ni tí a ti fún ní ìkarahun ìgbín, iyẹ̀pẹ̀, àti igi tíyóò fi tàn án ká fún iṣẹ́ pàtàkì náà..
wikipedia
yo
Ìtàn yí ni àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ Yorùbá gbàgbọ́ tí wọ́n sì fi ṣe ọ̀pákú ì)àgbọ́ wọn nípa ìṣẹ̀dá ayé..
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń fi igbá àti ṣe àmì Ọbàtálá àti Odùduwà nígbà tí Oriori igbá ń rọ́pò Ọbàtálá ti ìyá igbá sì ń dúró fún Odùduwà gẹ́gẹ́ bíese Olófìn Ọ̀yéte tí ó túmọ̀ sí ẹni tí gba igba iye lọ́dọ̀ Elédùmarè.Ẹ tún le wo àtòjọ àwọn ọba alayé Ilé-Ifẹ̀ àwọn Akon ìgbà ìwáṣẹ̀ tilẹ̀ àtikaàwọn ìtọ́ka ṣíwọ́ ìwọ̀n náàliàṣeyọrí Odùduwà kópa ojú ojúadé, J..
wikipedia
yo
Ifá jẹ́ òrìṣà kan pàtàkì láàarín àwọn Yorùbá àwọn Yorùbá gbàgbọ́ wipé Olódùmarè ló rán Ifa wá lati òde ọrun lati wá fi ọgbọ́n rẹ̀ tún ilé ayé ṣe..
wikipedia
yo
Ọgbọ́n ìmọ̀ àti òye tí Olódùmarè fi fún Ifá ló fún Ifá ni ipò ńlá láàárín àwọn ìbò ilẹ̀ Yorùbá …A kéré-finú-ṣọgbọ́n-ṣọgbọ́n"ní oríkì Ifá..
wikipedia
yo
Eleyí ló fi hàn wá gẹ́gẹ́ bí Abimbola (1969) ti gbé Kala.Nínú iṣẹ́ àgbékalẹ̀ ilésanmí Ó wá jẹ́ kí a mọ̀ wípé ifá ni alárinà fún gbogbo ọmọ Oòduà òun ni ó dàbí agbẹnusọ fún gbogbo àwọn òrìṣà àti Olódùmarè ọ̀hún sí la kà sí ẹni tó ń ṣe ajẹ́wọ̀ fún gbogbo mùtúmùwà..
wikipedia
yo
Èyí wà fún ní ìbò aṣojú fún gbogbo àwọn irúnmọlẹ̀ yóòkù..
wikipedia
yo
Ifá jẹ́ ewì tí ó máa ń lò láti ìlú kan sí èkejì láti dÍfá..
wikipedia
yo
Èyí ló ṣe okùnfà bíbá ọ̀pọ̀ obìnrin pàdé ó sì fún ní àǹfààní láti fẹ́ ìyàwó púpọ̀ torí irúfẹ́ iṣẹ́ tí ìfà ń ṣe..
wikipedia
yo
Èyí sì ló fà tó fi ṣẹ̀ṣẹ̀ fún ìfà láti mọ ìwà wọn ó wu onírúurú ìwà yìí jáde torí àjọṣepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn obìnrin..
wikipedia
yo
Gbogbo ibi tí ìfà bá ti dé ló ti ń yan ìyàwó, èyí ló mú Ifá rí àrísà àwọn obìnrin..
wikipedia
yo
Obìnrin ni a lè pè ní ìdàkejì ọkùnrin tí a bá wo tíọ́rì àbùdá oníbejì fún àgbéyẹ̀wò lítíréṣọ̀ ifá tí ilẹ̀sàmì pajúbà rẹ̀ Tíọ́rì yìí ni ó jẹ́ kí a mọ̀ pé láìsí ọ̀tún òsì kò lè dádúró..
wikipedia
yo
Èròǹgbà ópilẹ̀kọ́ yìí ni láti tan ìmọ́lẹ̀ sí ipò tí ifá fi àwọn obìnrin sí àkíyèsí àwọn ipò wọ̀nyí sì hàn nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ifá..
wikipedia
yo
Ojú méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni ìfà fi wo àwọn obìnrin (i)ó rí wọn gẹ́gẹ́ bí ẹni rere tí kò ṣe mánìyẹn tó lẹ́wà..
wikipedia
yo
(ii)Ifa ri àwọn obìnrin ní ìdàkejì gẹ́gẹ́ bi olùdarí tàbí Olubi ẹdá..
wikipedia
yo
Àwọn obìnrin la bá máa pè ní ẹjọ́ gẹ́gẹ́ bí àgbékalẹ̀ ìfà..
wikipedia
yo
Nítorí ìdí èyí ifá rọ àwọn ọkùnrin láti gbọ́n nínú gbọ́n lóde tí ọ̀rọ̀ bá ti di ọ̀rọ̀ obìnrin.Obìnrin gẹ́gẹ́ bíi koṣeemani tàbí ẹni rerenínú ìpín yìí ifá bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe àfihàn wọn láti òde pé wọ́n tẹ̀wá ó sì rí obìnrin gẹ́gẹ́ bí ẹni rere..
wikipedia
yo