cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Tí a bá ṣẹ̀ yí, a ó wá fi ẹ̀rún ti kún àpólà-iṣẹ́ náà..
wikipedia
yo
Tí a bá lọ o pẹ̀lú ibá-ìṣẹ̀lẹ̀ àdáwà, kò sí wúnrẹ̀n tó máa ń tọ́ka rẹ̀..
wikipedia
yo
máa ń àti a máa lọ máa ń tọ́ka ìba-ìṣẹ̀lẹ̀ yìí nínú yá..
wikipedia
yo
ọ̀ná tí éí ń gbà tọ́ka ìba-ìṣẹ̀lẹ̀ yìí yàtọ̀ gẹ́gbègbé sí ti ya..
wikipedia
yo
A máa ń lò ó papọ̀ pẹ̀lú atọ́ka ibá-ìṣẹ̀lẹ̀ atẹ́rẹrẹ 43(i)Olú ẹ̀ẹ̀ tí loolle ti lọ(ii)Olú tí ń lọ44(i)an an tí ká kọrin (ii)wọ́n a ti máa kòguèé ní atọ́ka ìyísódì ibá-ìṣẹ̀lẹ̀ yìí..
wikipedia
yo
Nígbà tí a bá yìí pada, ohùn ààrin tó wà bẹ lórí atọ́ka ibà-ìṣẹ̀lẹ̀ náà yóo yí pada sí ohùn ìsàlẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn múudú wọ̀nyí ni à ń dá pé ní ojúṣe lórántí, àníyàn àti kànńpá lédè Yorùbá..
wikipedia
yo
ÈÉ ní atọ́ka ìyísódì ojúṣe nínu éí.62(i)Olú ẹ̀ẹ́ Lee joba Uulu rẹ̀ (ii)Olú kò lè joba ìlú Reìyísódì ojuse kànńpágbeedo ni atọ́ka ojuse kànńpá ninu éí..
wikipedia
yo
Fetomi (2001) ni tirẹ̀ ṣàlàyé wí pé ojúṣe ni yóò àti àwọn ẹ̀dá rẹ̀, ṣùgbọ́n ó ní Yorùbá tún máa ń lò wọ́n láti fi tọ́ka sí àsìkò ọjọ́-iwájú..
wikipedia
yo
Oyelaran (1982) Ninu ero rẹ ko fara mọ́ ero pe yoo jẹ atọ́ka àsikò Ojo-iwaju..
wikipedia
yo
O ní yóo máa ń ṣiṣẹ́ ìba-ìṣẹ̀lẹ̀, o sì tún máa ń ṣiṣẹ́ ojúṣe nígbà mìíràn..
wikipedia
yo
ṣaláìwù (2005) o gba yoo gege bi Atọka asiko Ojo-iwaju tabi ojuse..
wikipedia
yo
Ó ní yóo ati àwọn ẹ̀dá rẹ̀ a, ó ati óo jẹ́ atọ́ka ìba-ìṣẹ̀lẹ̀ àníyàn ninu ya..
wikipedia
yo
Adewọlé (1988) ní tirẹ̀ ṣe orinkiniwin alàyè láti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé atọ́ka múudù ni yóò..
wikipedia
yo
Nítorí náà, a ó lo wúnrẹ̀n yóò gẹ́gẹ́ bí ojúṣe àníyàn..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n, tí ọ̀rọ̀-ìṣe bá ju ọ̀kan, tàbí tí àpólà-iṣẹ́ bá ní fọ́nrán tí ó ju ọ̀kan lọ, a lè ṣe ìyísódì fọ́nrán ìhun tàbí tí odidi gbólóhùn.ìyísódì gbólóhùn alàyègbólóhùn alàyè ni a máa ń lò láti fi sọ bí nǹkán bá ti rí..
wikipedia
yo
Àwọn àpẹẹrẹ gbólóhùn aṣe ni71(i) Waipasẹ̀14)Sáré wa!72(i) ka Lonírú Lo-ìyísódì (ìyísódì (71) yóò fún wa ní (73i73i) hare wa (ii)má sáré síke a bá fẹ́ ṣe ìyísódì (72), a ó yọ atọ́ka ibá-ìṣẹ̀lẹ̀ atẹ́rẹrẹ ká kúrò, a ó sì lo atọ́ka ìyísódì máà dípò rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó ní ọ̀nà tí à ń gbà ṣe èyí ni pé kí a lo wúnrẹ̀n ìbéèrè nínú gbólóhùn.A ó ṣe àgbéyẹ̀wò wọn lọ́kọ̀ọ̀kan àti bí ìyísódì ṣe ń jẹ yọ pẹ̀lú wọn.Gbólóhùn ìbéèrè tí ó ń lò atọ́nà gbólóhùnṣe ni éí máa ń lò gẹ́gẹ́ bí atọ́nà gbólóhùn láti fi ṣe ìbéèrè bẹ́ẹ̀-ní-bẹ́ẹ̀-kọ́..
wikipedia
yo
Ó ní ọ̀rọ̀-orúkọ aṣeẹ̀ka ni èyí tí a lè lò pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ònkà nítorí pé irú ọ̀rọ̀-orúkọ bẹ́ẹ̀ ṣe é kà.Ní ìbámu pẹ̀lú èrò Bámgbóṣé yìí, tí a bá lo ọ̀rọ̀-orúkọ àṣẹẸ̀ka pẹ̀lú Ọ̀rọ̀-òǹkà papọ̀, yóò fún wa ní àpólà-orúkọ..
wikipedia
yo
Àtúpalẹ̀ irúfẹ́ àpólà-orúkọ yìí ní orí (tii ṣe ọ̀rọ̀-orúkọ) àti èyàn rẹ̀ (ọ̀rọ̀ ònkà náà)..
wikipedia
yo
Irúfẹ́ àpólà-orúkọ yìí maa ń ṣáábà wáyè nínú àpólà-orúkọ tí ọ̀rọ̀ ònkà jẹ́ èyàn rẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ṣá, kì í ṣe pé àpólà-orúkọ náà kò ní orí; mọ̀ọ́nú ní orí àpólà náà, ó sì yé àwọn méjèèjì tó bá ń tàkúrọ̀sọ..
wikipedia
yo
ÈÉ ṢE ni a fi maa ń yí irúfẹ́ àpólà-orúkọ agerí wọ̀nyí nínú éí..
wikipedia
yo
A ṣe akiyesi oniruuru ìhun tí ìyísódì tí ń jẹ yọ nínú éí..
wikipedia
yo
A jẹ́ kó di mímọ̀ pé a lè ṣe ìyísódì ẹyọ ọ̀rọ̀; a lè ṣe ìyísódì fọ́nrán ìhun gbólóhùn, a sì lè ṣe ìyísódì odidi gbólóhùn..
wikipedia
yo
A tún ṣe àgbéyẹ̀wò ìyísódì àsìkò, ìba-ìṣẹ̀lẹ̀ àti ojúṣe nínú éí.Lẹ́yìn èyí, ọwọ́jà iṣẹ́ yìí dé àgbéyẹ̀wò ònkà éí..
wikipedia
yo
A ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ọrọ ònkà náà gẹgẹ bí èyàn ẹ̀sìngkà, a sì ṣe àfihàn bí a ṣe n ṣe ìyísódì ònkà éí...
wikipedia
yo
Ojú ewé ìmọ̀ ìṣiròìmọ̀ ìṣírí jẹ́ èyí t'on jẹ mọ́ nípa ọ̀pọ̀Iye (quantity), nípa ọ̀pọ̀ (Structure), nípa ìyípadà (Change) àti nípa ààyẹ̀ (Space)..
wikipedia
yo
Ìdàgbàsókè ìmọ̀ ìṣirò wà nípa lílo afòyemọ̀ọ́ (ABstction) àti Ìrubn Ìrònú, pẹ̀lú ònkà, ìṣèṣirò, wíwọn àti Nípa Fi Fi Ètò S'àgbéyẹ̀wò Bí Àwọn Ohun Ṣe Rí (shaÀṣẹ) àti Bí Wọ́n Ṣe Ń Gbéra (Motion)..
wikipedia
yo
Eyi ni àwọn onimo iṣiro n gbéyẹ̀wò, ero won ni lati wa aba tuntun, ki wọn o si fi óna re mule pẹlu itumọ yékéyéké.A n lo ìmọ̀ iṣiro ka kiri agbaye ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọna ninu imo sayensi, imo iṣe ẹrọ, imo iwosan, ati imo ọrọ̀ okowo..
wikipedia
yo
Bí a ṣe ń lọ ìmọ̀ ìṣirò bọ́ sí apá èyí tí à ń pè ní ìmọ̀ ìṣirò lílo (Applied AcJesus)..
wikipedia
yo
Èyí jẹ mọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìṣirò tó kọ́ ti ní ìlò kankan bó tilẹ̀jẹ́ pé ó ṣe ṣẹ̀ kí a wá ìlò fún ní ẹ̀yìnwá ọ̀la...
wikipedia
yo
Ojú ewé ìmọ̀ ìṣiròìmọ̀ ìṣirò jẹ́ èyí t'on jẹ mọ́ nípa ọ̀pọ̀ (Ququantity), nípa ọ̀pọ̀ (Structure), nípa ìyípadà (Change) àti nípa ààyẹ̀ (Space)..
wikipedia
yo
Ìdàgbàsókè ìmọ̀ ìṣirò wa nípa lílo afòyemọ̀ọ́ (ABstction) àti ọgbọ́n Ìrònù, pẹ̀lú ònkà, ìṣèṣirò, wíwọn àti nípa fi fi ètò s'àgbéyẹ̀wò bí àwọn ohun ṣe rí (shaÀṣẹpẹ̀s) àti bí wọ́n ṣe ń gbéra (motion)..
wikipedia
yo
Èyí ni àwọn onímọ̀ ìṣirò ń gbéyẹ̀wò, èrò wọn ni láti wa àbá tuntun, kí wọn ó sì fi òótọ́ rẹ̀ múlẹ̀ pẹ̀lú ìtumọ̀ yékéyéké.À ń lo ìmọ̀ ìṣirò kà kiri àgbáyé ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà nínú ìmọ̀ Sáyẹ́ńsì, ìmọ̀ iṣẹ́ ẹ̀rọ, ìmọ̀ ìwòsàn, àti ìmọ̀ ọ̀rọ̀ okòwò..
wikipedia
yo
Bí a ṣe ń lọ ìmọ̀ ìṣirò bọ́ sí apá èyí tí à ń pè ní ìmọ̀ ìṣirò oníwúlò (Applied AcJesus)..
wikipedia
yo
Èyí jẹ mọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìṣirò tó kọ́ tì ní ìlò kankan bó tilẹ̀jẹ́ pé ó ṣe ṣe kí a wá ìlò fún ní ẹ̀yìnwá ọ̀la.
wikipedia
yo
Àwọn oriṣiriṣi nọ́mbà tí ó wánòmba àkókò nọ́ḿbà pípẹ́ nọ́ḿbà ṣíṣekú nọmba interpret nọmba apáòsì nọmba apa apa nọmba àdàbà nọmba odidi Àwọn ẹ̀ka ìmọ̀ Ìṣirò..
wikipedia
yo
Jeremiah Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ tí a bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta (Ẹrẹ́nà) ọdún 1909, tí ó sì kú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù karùn-ún (Èbìbì) ọdún 1987, jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti ẹ̀yà Yorùbá..
wikipedia
yo
Awólọ́wọ̀ jẹ́ olórí fún àwọn ọmọ ilẹ̀ Yorùbá àti ọ̀kan nínú àwọn olóṣèlú pàtàkì ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìgbà èwe a bí i ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 1909 ni ìkẹ́nnẹ́ tó wà ní ìpínlẹ̀ Ògùn lónìí..
wikipedia
yo
Ọmọ Agbé tí ó fi iṣẹ́ àti ìrúkò isẹ́ sọ ara rẹ̀ di ọ̀mọ̀wé, Awólọ́wọ̀ lọ Ilé ẹ̀kọ́ Anglican àti Methodist ní Ikenne àti sí Baptist Boys’ High School ní Abeokuta..
wikipedia
yo
Leyin re o lo si Wesley College ni Ibadanti o fi igba kan je-ilu-ilu agbegbe agbegbeiwoorun Naijirialati ba di olukọ lori olukọ..
wikipedia
yo
Ó ṣe olùdarí àti alákòóso ẹgbẹ́ olùtajà àwọn ọmọ Nàìjíríà (Nigerian produce traders Association) àti akọ̀wé gbogbogbòò ẹgbẹ́ àwọn awakọ̀ ìgbẹ́rù ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà (Nigerian Motor Transport Union)..
wikipedia
yo
Awólọ́wọ̀ tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó sì gba ìwé ẹ̀rí kékeré ní ọdún 1939, kí ó tó lọ láti gba ìwé ẹ̀rí ẹ̀kọ́ gíga nínú ìmọ̀ owó ní ọdún 1944..
wikipedia
yo
Ìgbà yìí náà ló tún jẹ́ olóòtú fún ìwé ìròyìn òṣìṣẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà (Nigerian Wor)..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1940 ó di akọ̀wé ẹgbẹ́ ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà (Nigerian Youth Movement) Ẹ̀ka Ìbàdàn, ibi ipò yìí ni ó ti ṣolórí Itírà láti ṣe àtúnṣe ìgbìmọ̀ aláṣẹ ìdámọ̀ràn fún àwọn ọmọ Ìbàdàn (Ibadan Native Authority Advisory Board) ní ọdún 1942.ìṣèlú ní ọdún 1944 ó lọ sí ìlú Londonu lákì kọ́ ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ òfin bẹ́ẹ̀ ni ó sì dá ẹgbẹ́ ọmọ Odùduwà sílẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ọdún 1947 ó darí padà wálé láti wá di agbẹjọ́rò àti akọ̀wé àgbà fún ọmọ ẹgbẹ́ Odùduwà..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọdún meji, Awólọ́wọ̀ ati àwọn asíwájú Yoruba yòókù dá ẹgbẹ́ òṣèlú Action Group sílẹ̀, èyí tí ó borí ninu ìbò ọdún 1951 ní agbègbè ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Láàárín ọdún 1951-54 Awólọ́wọ̀ jẹ́ alákòóso fún iṣẹ́ ìjọba àti ìjọba ìbílẹ̀, ó sì di Olórí ìjọba agbègbè ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 1954 lẹ́yìn àtúnkọ ìwé ìgbépapọ̀ àti òfin (Constitution).Gẹ́gẹ́ bí Olórí Ìjọba agbègbè ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà, Awólọ́wọ̀ dá Èkó ọ̀fẹ́ sílẹ̀ fún gbogbo ọ̀dọ́ láti rí i pé mọ̀ọ́kọ-mọ̀ọ́ká gbà le ka.jàgídíjàgan ní apá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà Nígbà tí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà gbòmìnira ní ọjọ́ kìíní oṣù Kẹwàá ọdún 1960, Awólọ́wọ̀ di olórí ẹgbẹ́ alátakò (opposition leader) sí ìjọba Abubakar Tafawa Balewa àti Ààrẹ Nnamdi Azikiwe ní ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Aíyọ tó wà láàárín òun àti Samuel Ladoke Akintola tó dìpọ̀ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí gbé he olórí ìjọba ní agbègbè ìwò oòrùn mú ni ó dá fà ka ja tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 1962..
wikipedia
yo
Ní oṣù kọkànlá ọdún yìí, ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà fi ẹ̀sùn kan Awólọ́wọ̀ wí pé ó dìtẹ̀ láti dojú ìjọba bolẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbẹ́jọ́ ó tó oṣù mọkanla, ilé-ẹjọ́ dá Awólọ́wọ̀ ati àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú rẹ̀ mejidinlọgbọn lẹ́bi ẹ̀sùn ìdìtẹ̀, wọ́n sì rán wọn lẹ́wọ̀n ọdún mẹ́wàá..
wikipedia
yo
Ọdún Mẹ́ta péré ni ó lọ ní ẹ̀wọ̀n ní ìlú Kalaba ti ìjọba ológun Yakubu Gowon fi dá sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹta Oṣù Kẹjọ ọdún 1966..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí Awólọ́wọ̀ di alákòóso ìjọba àpapọ̀ fún ọrọ̀ okòwò..
wikipedia
yo
Ni odun 1979 Awolowo da egbe oselu kan, egbe oselu Imọlẹ, sile.Aláìsí Obafemi Awolowo ṣaláìsí ni ojo Aiku ojo Kesan-an osu karun-un odun 1987 ni ilu ìkẹ́nnẹ́..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ikú Awólọ́wọ̀ Ìjọba àpapọ̀ yi orúkọ ilé ẹ̀kọ́ giga Ilé-Ifẹ̀ padà si Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University..
wikipedia
yo
oore (ADV); nínú ọkọ ojú omi tàbí òfúrufú; the Captain Welcomes you aboard this plane..
wikipedia
yo
ọlọb (AD); Ko si, Ko wa; he was absent from work last Tuesday..
wikipedia
yo
absolute (AD€); pátápátá; Ámínádì has absolute Freedom to Surhi a Husband..
wikipedia
yo
Acint (v) dáláre, dasilẹ the suspect was actationsted by the Court (Ilé Ẹjọ́ Dá Arúfin naa sile)..
wikipedia
yo
(Ọ̀kan lára àwọn òṣèrébìnrin ìwòyí ni Liz Benson n ṣe)..
wikipedia
yo
(A kọ́ ilé ìjọ́sìn yìí ní ẹgbẹrun meji ọdún ó dín díẹ̀ lẹ́yìn ikú Oluwa wa)..
wikipedia
yo
(Ó máa ń sọ̀rọ̀ nígbà míràn kí ìgbé ayé ìgboro to Mọ́mì lára)..
wikipedia
yo
(Ẹ̀yindíye meje ló wà ninu apẹ̀rẹ̀, mo fi mẹta kún un, ní bá yìí ó ti di mẹ́wàá..
wikipedia
yo
O lè dá Romu, kí o sì ṣe ìpinnu lórí ohun tí ó kàn án..
wikipedia
yo
advertise (v) Kéde, polówó; the supermarket was advertising Salt at a good price..
wikipedia
yo
(Òfin tuntun yìí kò kàn ní torí pé mò ń fi ilé ìwé náà sílẹ̀..
wikipedia
yo
(Baba mi ni àwọn kò ní agbára láti ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́)..
wikipedia
yo
(Mo gbádùn ìwé náà tó bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ tó jẹ́ pé mo tún un ka)..
wikipedia
yo
(iṣẹ́ àgbẹ̀ ṣe pàtàkì nítorí wí pé gbogbo wa ni a máa jẹun)..
wikipedia
yo
(Ìwé Aṣọtúmọ̀ jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún kíkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì)..
wikipedia
yo
(Ó gbèrò láti jẹ́ òṣèré orí pápá tí ó dára jùlọ ní ilé ìwé)..
wikipedia
yo
Wọ́n pa erin ibi ti erin náà kú sí ibà ni wọ́n pè ní àtẹ̀bá ẹni tó pa erin náà ni ọlọta àbúrò ìjìṣe ibi tí wọ́n pa erin náà sí ni wọ́n pè ní ìjìṣe..
wikipedia
yo
Ìjìṣe ló pa àwọn ará oyè wa láti ilé Ifẹ̀ pé wọ́n ti rí ibi tí wọ́n fẹ́ràn..
wikipedia
yo
Ìgbátí wọn dé ìlú oyè wọ́n sit ún pè wọ́n ní ìjàgémọ́ nítorí ìjà wọn..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ yìí ló ṣe wá sí ìlú oyè Ìdí tí wọ́n fi tẹ̀dó sí ìlú oyè ní èyí.Yorùbá Èkìtì..
wikipedia
yo
(títí di irun orí rẹ̀ ní òwú dúdú).11.id= (n); irun dídì..
wikipedia
yo
(Afara náà ti yẹ33.Bridge (verb); Safara sì he formed a bridge on the water..
wikipedia
yo
92.By (Preposition); lẹ̀bàá; my house is by the river..
wikipedia
yo
Orúkọ Bàbá yí ni wọ́n fi wá ń pe àdúgbò yí ní ìṣdọ̀..
wikipedia
yo
lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́oṣù kínní ní January jẹ́ nínú kàlẹ́ńdà Gregory..
wikipedia
yo
Ọjọ́ méjìdínlọ́gbọ̀n tàbí mọ́kàndínlọ́gbọ̀n ni ó wà nínú February...
wikipedia
yo
Oṣù kẹta (tí àwọn Yorùbá mọ̀ sí oṣù Ẹrẹ́nà) jẹ́ oṣù kẹta ọdún lẹ́nda gírẹ̀rí àti Julian..
wikipedia
yo
Òun ní oṣù kejì nínú àwọn oṣù méje tí ó ní ọjọ́ mọ́kànlélógún...
wikipedia
yo
Abubakar Tafawa Balewa (December 1912 – January 15, 1966) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, lati apá àríwá ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Balewa jẹ́ alakoso agba (Prime minister) akọkọ fun ile Naijiria ni igba oselu akoko ile Naijiria leyin igba ti Naijiria gba ominira ni odun 1960..
wikipedia
yo
Eni àyẹ́sí ni kariaye, o gba owo ni orile Afrika gege bi ikan lara awon ti won Daba idasile àkójọegbe okan ara Afrika (organization of African Unity, OAU).Igba Ewe ati ise-itọkasiji awon olori ile Naijiria..
wikipedia
yo
Oṣù Ọpẹ́ nínú òǹka Oṣù ojú ọrùn Yorùbá ni ó jẹ́ Oṣù kejìlá nínú òǹkà Oṣù Ojú ọ̀run ti àwọn (gẹ̀ẹ́sì) tí wọ́n pè ní December ọjọ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni ó wà nínú Oṣù yí..
wikipedia
yo
Oṣù December ni àwọn Gẹ̀ẹ́sì fa orúkọ rẹ̀ yọ látara ọ̀rọ̀ ""Oòos" (tí ó túmọ̀ sí Ten) nítorí wípé òun gaan ní oṣù Kẹwàá ọdún nínú kalẹ̀dá ti àwọn Calendar of Romulus ti ìbẹ̀rẹ̀ oṣù tiwọn sì bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹta ọdún..
wikipedia
yo
Àwọn oṣù tókù kò ti sí tẹ́lẹ̀, àmọ́ wọ́n ṣàfikún oṣù kinni àti oṣù kejì kún ti December sì dá dúró ní tirẹ̀.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Ninu imo iṣiro nọmba akoko (Prime Number) ni a si awọn nọmba adabayé (Natural Numbers) ti wọn ni nọmba àdàbà meji perẹ̀ẹ́ ti a le fi pin wọn dọgba, eyi ni Nobabaa 1 ati nọmba akọkọ fun ara rẹ..
wikipedia
yo
Awon nọmba akoko po to bee to fi je wipe won ko lopin gegee bi EFK][A se fihan ni ọdúnn 300 K.J (kia to bi Jésù, K.J)..
wikipedia
yo
Ṣe ìsọdipúpọ̀ gbogbo m, kí o sì ṣe arọ́pò rẹ pẹ̀lú ọkàn (nọ́ḿbà eftapépé)..
wikipedia
yo
Nọmba eyi ti ri ko ṣe pin pẹlu Ìkójọpọ̀ Number akoko kankan t'ọlọ, nitoripe bi a ba ṣe pin to ọkan yio ṣeku, bẹ síni ọkàn ko ṣe pin pẹlu nọmba akọkọ..
wikipedia
yo
Nípa báyĩ, tàbí kí ó jẹ́ nọ́ḿbà àkókò fún ra ara rẹ̀ tàbí kí ó ṣe pín pẹ̀lú nọ́ḿbà àkókò míràn tí kò sí nínú ìkójọpọ̀ tó l'òpin..
wikipedia
yo
Lumberka, a gbúdọ̀ ni nọmba akoko ti yio jẹ m + 1.awọn nọmba..
wikipedia
yo
Ninu Mathematiki, awon nọmba adabayé, tabi nọmba àdàbà (Natural Number) le jẹ ọkan ninu akojọpọ {1, 2, 3,} (yun nọmba odidi rere) tabi ọkan ninu akojọpọ {0, 1, 2, 3, ...} (yun gbogbo nọmba ti ki ṣe ti odi).A n lo nọmba àdàbà fun kika ("ọsan mẹfa lowá ninu apẹrẹ yi); bẹ ni a si tun n lo wọn fun sise eto elesẹ ("ipo keji ni Bukola mu ninu idije Saeti ọdun yi"). ; nọmba..
wikipedia
yo
Mathemátì tàbí ìmọ̀ ìṣirò jẹ́ èyí t'ọ́n jẹ mọ́ nípa ọ̀pọ̀ (Ququantity), nípa ọ̀pọ̀ (Structure), nípa ìyípadà (Change) àti nípa ààyè (Space)..
wikipedia
yo
Ẹ ní àwọn onímọ̀ ìṣirò ń gbéyẹ̀wò, èrò wọn ni láti wa àbá tuntun, kí wọn ó sì fi òótọ́ rẹ̀ múlẹ̀ pẹ̀lú ìtumọ̀ yékéyéké.À ń lo ìmọ̀ ìṣirò kà kiri àgbáyé ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà nínú ìmọ̀ Sáyẹ́ńsì, ìmọ̀ iṣẹ́ ẹ̀rọ, ìmọ̀ ìwòsàn, àti ìmọ̀ ọ̀rọ̀ okòwò..
wikipedia
yo
Eyi jẹ mọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìṣirò tó kọ́ ti ni ìlò kankan bó tilẹ̀jẹ́ pé ó ṣe ṣẹ̀ kí a wá ìlò fún ni ẹ̀yìnwá ọ̀la.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo