cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Kí wọ́n tó lọ, wọ́n pín ẹrù tàbí ohun ìní bàbá wọn láìfi nǹkan kan sílẹ̀ fún àbúrò wọn - Ajíbógun..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ó dé, ó bu omi òkun bọ̀, wọ́n lo omi yìí, baba wọn sì ríran..
wikipedia
yo
Ojú Ajíbógun korò, inú sì bi pé àwọn ẹ̀gbọ́n òun ti fi bàbá wọn sílẹ̀ tí wọ́n sì kó ohun inú rẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
“Ọmọ àlè ní í rínú tí kì í bí, ọmọ àlè la ń bẹ̀ tí kì í gbọ́” báyìí ló gba ìpẹ́ (ẹ̀bẹ̀ bàbá rẹ̀..
wikipedia
yo
Agígírì fẹ́ràn ajíbogun Ọwá Obokun púpọ̀ nítorí pé ọmọ ìyá rẹ̀ ni..
wikipedia
yo
Láti fi ilé - ìfẹ́ sílẹ̀ kí wọ́n sì wá ibùjókòó tuntun fún ara wọn níbi tí wọ́n yóò ti máa ṣe ìjọba wọn..
wikipedia
yo
Ọwá gba Òdu lọ, Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà sì gba Ilékéte lọ..
wikipedia
yo
Agóró yìí ló dúró sí tí ó fi rán Lúmọ̀ogun akíkanju kan patàkan nínú wọn tí ó tẹ̀ lé e pé kí ó lọ sí iwájú díẹ̀ kí ló wo ibi tí ilẹ̀ bá ti dára tí àwọn lè dó sí..
wikipedia
yo
Igbà ti Agígírì kò rí Lúmọ̀ogun, ominú bẹ̀rẹ̀sí í kọ́ ọ́, bóyá ó ti ṣọnù tàbí bóyá ẹranko búburú ti pá jẹ..
wikipedia
yo
Ibi tí wọ́n ti ń wá a kiri ni wọ́n ti gbúròó rẹ̀ ni ibì kan tí a ń pè ní Òkènísà ni Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà lónìí yìí..
wikipedia
yo
Eléyìí ni wọ́n ṣe máa ń pe òkèkè tí wọ́n dó sí yìí ní orí ayé..
wikipedia
yo
Agbo ilée Bajimọn ní Òkè - Ọjà ni Agígírì kọ́kọ́ fi ṣe ibùjókòó..
wikipedia
yo
Kò pẹ́ púpọ̀ lẹ́hìn èyí ni ó bá lọ jà ogun kan, ṣùgbọ́n kí ó tó padà dé, ọmọ rẹ̀ kan GVA Ósún ńlá kan jọ tí ó fi jẹ́ wí pé Agígírì kò lè padà sí ilée Bajimọ mọ́..
wikipedia
yo
Ilédè ni Agígírì kọjá sí láti lọ múlẹ̀ tuntun tí ó sì kólé sí ilédè náà ni ibi tí ààfin Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà wà títí di òní yìí..
wikipedia
yo
Ó jókòó níbẹ̀, ó sì pe àwọn tí ó sì jẹ́ olóòótọ́ sí i wọ́n múra láti gbé ogun ti ọmọ rẹ̀ náà títí tí wọ́n fi ṣẹ́gun rẹ̀..
wikipedia
yo
Níkẹhìn, ọmọ náà túnúnbá fún baba rẹ̀ ati àwọn ọmọ - ogun rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìtàn míràn bí a ṣe tẹ Ijẹ̀bù - Jẹ̀ṣà dò àti bí a ṣe mọ̀ ọ́n tàbí sọ orúkọ rẹ̀ ní Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ní ìtàn àwọn akíkanjú tàbí akọni ọdẹ méje tí wọ́n gbéra láti Ifẹ láti ṣe ọdẹ lọ..
wikipedia
yo
Wọ́n bẹ̀rẹ̀sí í tójùu rẹ̀ ìgbà tí wọ́n ṣe àkíyèsí wí pé ọgbẹ́ náà sàn díẹ̀, wọ́n tún gbéra, wọ́n mú ọ̀nà-àjò wọn pọ̀n..
wikipedia
yo
Ìga tí wọ́n dé ibi tí a ń pè ní Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà lónìí yìí ni ẹ̀jẹ̀ bá tún bẹ̀rẹ̀sí í sàn jáde láti ojú ọgbẹ́ ọkùnrin náà..
wikipedia
yo
Wọ́n bá dúró níbẹ̀ láti máa tọ́jú egbò náà, wọ́n sì dúró pẹ́ díẹ̀..
wikipedia
yo
Orúkọ tí Olórí wọn - Agígírì sọ ibẹ̀ ni Ìjẹ̀bú nítorí pé ìjẹ ni Ìjẹ̀ṣà máa ń pé ẹ̀jẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí ìyípadà sì ń dé tí ojú ń là á sí i ni wọ́n sọ orúkọ ìlú da Ìjẹ̀bú dípò Ìjẹ̀bú tí wọ́n ti ń pè é tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Agígírì yí ni Ọba Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà kìíni, àwọn ìran ọlọ́dẹ méje ìjọ́sí ló di ìdílé méje tí ń jọ́ba Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà títí di òní..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n Ijẹ̀bú - Ẹrẹ̀ ni wọ́n kọ́kọ́ máa ń pe ìlú yìí rí nítorí ẹrẹ̀ tí ó ṣe ìdènà fún àwọn Ọ̀yọ́ tí ó ń gbógun ti ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà nígbà kan..
wikipedia
yo
A níláti tọ́ka sí i pé Ìjẹ̀bú ti Ìjẹ̀ṣà yí lè ní nnkan kan í ṣe pẹ̀lú Ìjẹ̀bu ti Ìjẹ̀bù – Òde..
wikipedia
yo
Ìtàn le XXXX pa wọ́n pọ̀ nípa àjọjẹ́ orúkọ, àjọṣe kankan lè máà sí láàárin wọn nígbà kan ti rí ju wí pé orúkọ yìí, tó wu níbẹ̀ẹ̀rẹ̀ kìíní Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà nígbà tí ó bá àbúrò rẹ̀ Ajíbógun lọ bòkun, wọ́n gba ọ̀nà Ìjẹ̀bú – Òde lọ..
wikipedia
yo
Ibẹ̀ ló ti mú orúkọ yìí bọ̀ tí ó sì fi sọ ìlú tí òun náà tẹ̀dó..
wikipedia
yo
Nínú àwọn ìtàn òkè yí àwọn méjì ló sọ bí a ṣe sọ ìlú náà ní Ijẹ̀bú ṣùgbọ́n ó dàbí ẹni pé a lè gba ti irúfẹ́ èyí tí ó sọ pé Ìjẹ̀bú - Òde ni Ọba Ijẹ̀bú Jẹ̀ṣà ti mú orúkọ náà wá ní eléyìí tí ó bójú mu díẹ̀..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí ìtàn àtẹnudẹ́nu, oríṣìíríṣìí ọ̀ná ni a máa ń gbà láti fi ìdí òótọ́ múlẹ̀, ṣùgbọ́n ó kù sọ́wọ́ àwọn onímọ̀ òde òní láti ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn ìtàn wọ̀nyí kí a sì mú eléyìí tí ó bá fara jọ ọ̀ọ́tó jù lọ nínú wọn.Nípa pé tẹ̀gbọ́n tàbúrò ni Ọwá Iléṣà àti Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà jẹ́ láti àárọ̀ ọjọ́ wa yìí, sọ wọ́n di kòrí – kòsùn ara wọn..
wikipedia
yo
Ṣé bí ìgbín bá sì fà ìkarahun rẹ̀ a tẹ̀ lé e ni a máa ń gbọ́..
wikipedia
yo
ÌGBÀ TÍ Ó di wí pé àwọn tẹ̀gbọ́n tàbúrò yí máa fi Ifẹ́ sílẹ̀, ìgbà kan náà ni wọ́n gbéra kúrò lọ́hùnún, apá ibi Ken náà ni wọ́n sì gbà lọ láti lọ tẹ̀dó sí..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ wọn náà wá di tí a já tí kì í lọ kí kòrókòró rẹ̀ gbélé..
wikipedia
yo
Àjọṣe ti ó wà láàárìn wọ́n pọ̀ gan-an tí ó fi jẹ́ wí pé ní gbogbo ìlẹ̀ Ijẹ̀ṣà, Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà àti Ọwá Iléṣà jọ ní àwọn nnkán kan lápapọ̀ bẹ́ẹ̀ náà si ni àwọn ènìyàn wọn..
wikipedia
yo
Tí Ọwá bá fẹ́ fi ènìyàn bọrẹ̀ láyé àtijọ́, Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà gbọ́dọ̀ gbọ́ nípa rẹ̀..
wikipedia
yo
Tí Ọwá bá fẹ́ bọ̀gún, ó ní ipa tí Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà gbọ́dọ̀ kó níbẹ̀, ó sì ní iye ọjọ́ tí ó gbọ́dọ̀ lò ní Iléṣà..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ àgùnlégún, ìlù ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ni wọ́n máa n lù ní Iléṣa fún gbogbo àwọn àgbà Ìjẹ̀ṣà láti jó..
wikipedia
yo
Nígbà tí ọba ìgbàmọ̀ - Jẹ̀ṣà bá ń bộ wálẹ̀ lọ́pọ̀ ọ̀pọ̀ èbí tí ó ti lọ ní Ileṣa fún ọdún ogun, Ọtáforíjọ̀ ni àwọn ènìyàn rẹ̀ ti gbọ́dọ̀ pàdé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí wọ́n fi máa ń sọ pé; “ Káì bí an kọlijẹ̀bú an an tọ̀nà Ìjẹ̀ṣáá bo ọtájaja ọ̀nà ni an kọlijẹ̀bú ègbùrùkò èroko oyè ni wọ́n maa ń jẹ ni Iléṣà tí wọ́n sìn jẹ ni Ìjẹ̀bú Jẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
A rí Ògbóni ní Iléṣà bẹ́ẹ̀ náà ni ó wà ní Ìjẹ̀bú Jẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
Ara Ìwàrẹ̀fà mẹfà ni Ògbóni méjèèjì yí wà ní Iléṣà ṣùgbọ́n ọgbọ́n Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ni aṣáájú àwọn Ìwàrẹ̀fà náà..
wikipedia
yo
Bákan náà, oríṣìíríṣìí àdúgbò ni a rí tí orúkọ wọn bá ara wọn mu ní àwọn ìlú méjéèjì yí fún àpẹẹrẹ bí a ṣe rí ọgbọ̀n Ìlọ́rọ̀ ni Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà náà ni a rí i ní Iléṣà, Ọ̀kè wà ní Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà, Òkèsa sì wà ní Iléṣà..
wikipedia
yo
Odò-ẹsẹ̀ wa ni ìlú mejeeji yí bẹ́ẹ̀ náà ni ẹrẹ̀jà pẹlu..
wikipedia
yo
Nínú gbogbo àwọn ìlú tí ó wà ní ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà, èdè tàbí ohun tí Iléṣà àti ti Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ló bá ara wọn mu jù lọ..
wikipedia
yo
Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ló máa ń fi Ọwá tuntun han gbogbo Ìjẹ̀ṣà gẹ́gẹ́ bí olórí wọn tuntun lẹ́hìn tí ó bá ti ṣúre fún un tán.Tí ọ̀kan nínú wọn bá sì wàjà, òun ni ogún ti wọ́n máa ń jẹ lọ́dọ̀ ara wọn bí aya, ẹrù àti ẹrù ni ìgbà ayé ògún, ọ̀tún ògún, ni Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà jẹ́ ni ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà, wọ́n sì ní ọ̀nà tiwọn yàtọ̀ sí ti àwọn yòókù..
wikipedia
yo
Nígbà tí ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà dàrú nígbà kan láyé ọjọ́un, ẹlòmíràn-kùnrin Ọwá àti ẹlòmíràn-bìnrin Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ni wọ́n fi ṣe ètùtù kí ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà tó rójù ráyè, kí ó tó tábà tùṣẹ..
wikipedia
yo
Nítorí pé Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà àti Ọwá Iléṣà jẹ́ tẹ̀gbọ́n tàbúrò látàárọ̀ ọjọ́ wa, àjọṣe tiwọn tún lé ìgbà kan ju ti gbogbo àwọn Ọba ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà tó kù lọ nítorí pé “Ọwá àti Ògbóni Ìjẹ̀bù -Jẹ̀ṣà ló mọ ohun tí wọ́n jọ dì sẹ́rù ara wọn”.Yorùbá..
wikipedia
yo
Ìtàn bí agada Sende ìlú Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà méjì ló rọ̀ mọ́ bí agada ṣe dé Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà-Jẹ̀ṣà.Ìtàn kìínísọ fún wa pé ìlú ìláyé ni wọ́n ti gbé e wá sí Ijẹ̀bù - Jẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
Ìlú ìlaye yi ti wa lasiko kan ni ayé atijọ ṣùgbọ́n iwadii fi han wa pé kò sí i mọ lóde òní..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ pé Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà jẹ́ jagunjagun dídì tí ó lágbára púpọ̀..
wikipedia
yo
Ó jà títí ó lé àwọn ọ̀tá rẹ̀ kan dé ìlú iláyé, ṣùgọ́n kí ó tó dé ìlú yìí, àwọn ọ̀tá rẹ ti ranṣẹ sí àwọn eniyan wọn ní ìlú tiwọn pé kí wọn wá pàdé wọn láti fi agbára kún agbára fún wọn nítorí pé idẹ ń ta wọ́n lápá..
wikipedia
yo
Báyìí ni àwọn ènìyàn ọ̀tá Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà gbéra láti wá gbèjà Ọba wọn..
wikipedia
yo
Ìlú ìláyé yí ni wọ́n ti pàdé ọba ọ̀tá ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà, ogun sì wá gbóná janjan..
wikipedia
yo
Nítorí pé agbára ti kún agbára ọba ọ̀tá Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà yí, ó wá dàbí owó fẹ́ tẹ Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà àti àwọn ènìyàn rẹ̀ ni òun náà bá sá tọ ọba ìlú Ilaye lọ fún ìrànlọ́wọ́..
wikipedia
yo
Lọ́gán ni onítọ̀hún náà fún Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà ni òrìṣà kan nínú òrìṣà wọn tí ó lágbára gidi láti gbèjà Ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
Ṣugbọn ọba yìí kò gbé e fún un, ìlú rẹ̀ tí ń jẹ́ agada lọ gbé fún un láti máa gbé lọ ní ranti oriṣa olùgbèjà yí..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà dé ìlú rẹ̀ ni ó bá kọ́lé kan fún ìrántí òrìṣà yí ó sì fi ọkùnrin kan tí i pé kí ó máa bá òun rántí òrìṣà náà pé òun yóò sì wá máa fún un ní ewúrẹ́ kọ̀ọ̀kan lọ́dọọdún fún ìrántí oore tí ó ṣe fún wọn..
wikipedia
yo
Báyìí ni ó ṣe di ọdún Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà títí di òní, ìgbàkúgbà tí wọ́n bá sì fẹ́ rántí rẹ̀ tàbí bò ó, ìlú agada yìí ni wọ́n máa n lù fún un, ìlú ogun sì ni ìlú náà..
wikipedia
yo
Láti ọjọ́ náà tí ogun kan bá wọ ìlú Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà, ìlú náà ni wọ́n máa ń lù, tí wọ́n bá sì ti ń lù ú, gbogbo ọmọ -ogun ìlú ni yóò máa fi gbogbo agbára wọn jà nítorí pé orí wọn yóó máa ya, agbára sì làáyè máa kún agbára fún wọn.Ìtàn kejìsọ fún wa pé Ìjẹ̀bú -Jẹ̀ṣà ni wọ́n bi í àti pé alágbára gidi ni, ó fi gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ kà fim ìlù Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà, ṣùgbọ́n nígbẹ̀hìn ó kú gẹ́gẹ́ bí alágbára, wọ́n sì sin ín gẹ́gẹ́ bí akíkanjú ọkùnrin..
wikipedia
yo
Wọ́n sọ ọ́ di òrìṣà kan pàtàkì ní ìlú gẹ́gẹ́ bí àwọn alágbára ayé ọjọ́un tí wọ́n ṣe gudugudu méje yààyàà mẹ́fà fún àwọn ènìyàn wọn, tí wọ́n kú tán tí wọ́n sì ti ipa bẹ́ẹ̀ sọ wọ́n di òrìṣà àti ẹn Ibo lónìí àwọn òrìṣà bí ogun, Osun, Ṣàngó, Ọbàtálá àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ tí a ń gbọ́ orúkọ wọn jákèjádò ilẹ̀ Yorùbá lóde òní..
wikipedia
yo
Tí ogun bá sì wà, tí wọ́n bá ti ń lu ìlú náà, kí ó máa já lọ láìwọ eniyan ni..
wikipedia
yo
Kò sí sí ìgbà tí wọ́n bá ń lu ìlú yí tí ogun bá wà tí kò ní ṣẹ́gun..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ó sì kú, ìlú yí náà ni àwọn ọmọ Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà máa ń lù tí ogun bá wà, ó sì di dandan kí àwọn àá borí irú ogun bẹ́ẹ̀.Orúkọ míràn fún agada tún ní digúnmọ́ nítorí pé tí ogun bá ti ń bọ̀ láti wọ̀lú, ibi eréjàjà ni ọkùnrin akíkanjú náà yóó ti lọ pàdé rẹ̀, kò sì ní jẹ́ kí ó wọ ìlú dé apá òkèkè tí à ń pè ní orí ayé tí àwọn ènìyàn wà nígbà náà..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pè é ní digúnmọ́dò -di ogun mọ́ ọ̀dọ́..
wikipedia
yo
títí di òní yìí, èreja náà ni wọ́n ti ń bọ̀ ó gẹ́gẹ́ bí ojúbọ rẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn àgbà bọ́, wọ́n ní “Ejò kì í ṣe tara ẹni ká má mọ̀ ọ́n dá” èyí ló jẹ́ kí n ronú dáadáa sí àwọn ìtàn méjì yí láti lè mọ eléyìí tí ó jẹ́ òótọ́ tí a sì lè fara mọ́..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bi ìtàn àtẹnudẹ́nu, àwọn olùṣọ́tan ìtàn méjèèjì yí ló ń gbìyànjú láti sọ pé epo dùn ẹ̀fọ́ wọn nítorí pé oníkálukú ló ń gbé ìtàn tirẹ̀ lárugẹ..
wikipedia
yo
Akikanju ni òun náà tí kì í gbọ́ ẹkún ọmọ rẹ̀ kó má tinútinú wèrè” ní tirẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà kan rí, a gbọ́ wí pé oriṣa ìlú ejikú3 ni ìrókò jẹ́ ṣùgbọ́n ìgbà gbogbo ni ogun máa ń yọ ìlú yìí lẹ́nu tí wọ́n sì máa ń kó wọn lọ́mọ lọ..
wikipedia
yo
Nírànlì, wọ́n wá ìrànlọ́wọ́ wá sí ọ̀dọ̀ Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà ó sì ràn wọ́nm lọ́wọ́ láti ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá wọn..
wikipedia
yo
Nígbà tí ẹ̀kíkẹ̀jù rójú ráyè tán ni wọ́n bá kúkú kó wá sí ìlú Ìjẹ̀bú -Jẹ̀ṣà láti sá fún ogun àti pé ẹni tí ó ràn ní lọ́wọ́ yìí tó sá tó ìgbà tí ìlú méjì yí di ọ̀kan ni òrìṣà tí ó ti jẹ́ ti èjìkú tẹ́lẹ̀ bá di ti Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà nítorí pé ìgbà tí èjìkú ń bọ̀ wá sí Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà, wọ́n gbé òrìṣà wọn yìí lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Gbogbo ìgbà tí ogun bá dìde sí Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà náà ni Ìrókò yí máa ń dìde láti sa gbogbo ipa owó rẹ̀ láti gbèjà ìlú náà..
wikipedia
yo
Ológun gidi ni ìtàn sì sọ fún wa pé òun náà jẹ́ látàárọ̀ ọjọ́ wa..
wikipedia
yo
Ṣé ẹni tí ó ṣẹ̀ fún ni là ń ṣe é fún; èyí ni ìrókò náà ṣe máa ń gbé ọ̀rọ̀ Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà karí tí nǹkán bá dé sí i láti fi ìwà ìmoore hàn tún ìlú náà..
wikipedia
yo
Ìdílé kan pàtàkì ní èjìkú tí à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yí jẹ́ nílùú Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà lónìí, àwọn sì ni ìran ti ń sìn tàbí bọ òrìṣà Ìrókò yí..
wikipedia
yo
Olórí tàbí ọba èjìkú sì jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn Ìwàrẹ̀fà mẹ́fà Ọba Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà lónìí.Àwọn tínọ́nọ́n ń ṣe ọdún yíiléhìn ìgbà tí òrìṣà yí ijá i ìlú ìláyé dé Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà tí ọba sì ti gbé e kalẹ̀ sí eréjà, ló ti fi olùtọ́jú tì í..
wikipedia
yo
ọbalòrìṣà ní orúkọ rẹ̀ tí ô Jẹ agbátẹrù òrìṣà náà..
wikipedia
yo
“Ẹni tí ó sé fú ni là ń ṣe é fún” “Ẹni tí a sì ṣe lóore tí kò mọ̀ ọ́n bí a ṣe é ní ibi kò burú”kí àwọn ọmọ Ìjẹ̀bù - Jẹ̀ṣà má ba à jẹ́ abara – í moore – jẹ ni gbogbo wọn ṣe gba òrìṣà yí bí Ọlọ́run wọn tí wọ́n sì ń bọ ó lọ́dọọdún..
wikipedia
yo
Olórí àwòrò òrìṣà agada ní ọbalòrìṣà tí ó jẹ́ agbátẹrù òrìṣà náà..
wikipedia
yo
Aṣojú ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ló jẹ́ fún òrìṣà náà “Omi ni a sì ń tẹ̀ ká tó tẹ iyanrìn” bí ọba bá fẹ́ bọ agada, ọbalòrìṣà ni yóò ríi..
wikipedia
yo
Bí àwọn ọmọ ìlú ló fẹ́ bọ́ ọ, ọbalòrìṣà náà ni wọn yóò rí pẹ̀lú..
wikipedia
yo
isongbe ọbalòrìṣà nínú bíbọ̀ agada ni àwọn olórí ọmọ ìlú..
wikipedia
yo
Awon olori-omo yii lo maa n ko awon omo ilu lehin lákòókò odun agada naa lati jo yi ilu kaakiri ati lati maa ṣàdúrà fun ilọsiwaju ni gbobgo ìkóríta ilu..
wikipedia
yo
Òun ló ń pèsè ewúrẹ́ kọ̀ọ̀kan lọ́dọọdún láti fi bọ òrìṣà náà èyí wà ní ìbámu pẹ̀lú àdéhùn rẹ̀ ní ìgbà tó gba òrìṣà náà òun yóò máa fún un ní ewúrẹ́ kọ̀ọ̀kan lọ́dọọdún títí dòní ló sì ń ṣe ìrántí ìlérí rẹ̀ ọjọ́ kìíní..
wikipedia
yo
Wàyí o, gbogbo ìlú ni wọ́n ka ọdún dìde láti ṣe ọdún náà tọkùnrin tobìnrin, tọmọdé tàgbà..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà tí ó wà ní ìdálẹ̀ ni yóò wálẹ̀ fún ọdún náà..
wikipedia
yo
Gbogbo ìlú ló sì máa ń dùn yùngbà tí wọ́n bá ń ṣe ọdún náà lọ́wọ́.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Samuel Ladoke Akintola (July 6, 1906 – January 15, 1966) jẹ oloselu ọmọ orilẹ edè Naijiria lati ẹya Yoruba ni apa ila oorun..
wikipedia
yo
A bi ni ọjọ kefa osu keje ọdun 1906 ni ilu Ogbomosho.ibẹrẹ aye Kiku bi Samuẹli sinu idile Akintola ni ilu Ògbómọ̀sọ́, baba rẹ ni Akintola AkinBola nigba ti iya re n je Àkànkẹ́ Akintola..
wikipedia
yo
baba rẹ̀ jẹ́ oníṣòwò tí ó jáde wá láti inú ẹbí oníṣòwò..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó kéré jọjọ, àwọn ẹbí rẹ̀ kó lọ sí ìlú Minna tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Naija lónìí..
wikipedia
yo
Ó kàwé léjáde nílé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Church Missionary Society..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1922, ó padà wá sí Ògbómọ̀sọ́ láti wá bá bàbá bàbá rẹ̀ gbé tí ó tún tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ onítómitọ ṣáájú kí ó tún tó tẹ̀ síwájú ní ilé-ẹ̀kọ́ kọ́lẹ́ẹ̀jì ti onítẹ̀bọmi ní ọdún 1925..
wikipedia
yo
Ó ṣiṣẹ́ olùkọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Adèmí onítẹ̀bọmi láàrín ọdún 1930 sí 1942, lẹ́yìn èyí ni ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé iṣẹ́ àjọ tó mójú tó ìrìnà rélùwéè ní ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Davies, tí ó jẹ́ agbẹjọ́ro àti olóṣèlú, ó tún dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ ìtara Nigerian Youth Movement níbi tí ó ti ìṣàtìlẹ́yìn fún Ikoli láti di ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Ìgbìmọ̀ tó ń sojú ìpínlẹ̀ Èkó tako ní tí wọ́n yan Samuel Akisanya, ẹni tí Nnamdi Azikiwe fara mọ́ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí yoo dépò náà..
wikipedia
yo
Akintola tun dara po mo ile-iṣẹ iwe iroyin gege bi ko osise, ti o si di olootu fun.iwe iroyin naa ni odun1953 pelu atileyin ti o je okan lara okan awon olówó-iroyin naa ti o si rọpo Ernest Ernest Oloye olóòtú olóòtú..
wikipedia
yo
Akintola naa si da iwe-iroyin Yorùbá ti won n fi ede Yoruba gbe kale ni ojojumọ..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1945, o tako igbese idaṣe silẹ ti ẹgbẹ oṣelu NCC ti Azikiwe ati Michael Imo76, fẹ gun le, eyi si mu ki o di òdàlẹ̀ loju awọn oloselu bii Anthony Ayipada..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1946, Akintola rí ìrànwọ́ ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ gbà láti kàwé ọ̀fẹ́ ni U.K, níbi tí ó ti parí ìmọ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ nípa ìmọ̀ òfin, tí ó sì ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí agbẹjọ́rò lórí òfin tí ó jẹ mọ́ ìlú..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1952, oun ati Chris OgunBanjo,Oloye Bode Thomas ati Michael Odesanya kóra jo po di okan.itọkasiàwọn oloselu ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ninu imo Mathematiki, nọmba oniipin (kíkáonal Number) ni nọmba ti a le ko le gẹgẹ bẹ ipin nọmba odidi meji..
wikipedia
yo