cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
A le ko awọn nọmba oniipin ni ọpọlọpọ ọna, fun apẹrẹ , ṣugbọn o d'ẹrọ julọ nigbati a ati B ko ba ni nọmba kanna ti a le fi pin wọn a fi 1.awọn nọmba..
wikipedia
yo
Nínú Mathelanki, nọ́mbà asọ̀rọ̀ (Complex number) ni àwọn nọ́mbà tí wọ́n rí bayi tó jẹ́ pé a àti b wọ́n jẹ́ nọ́mbà gidi, tí í sì jẹ ẹyọ pápáyóò pẹ̀lú ìdámọ̀ bí i 2 = -1..
wikipedia
yo
Nọmba gidi a ni a n pe ni apa gidi nọmba tosoro, bẹ ṣini nọmba gidi b jẹ apa Àǹfàànítabi
wikipedia
yo
A le sọ pe awọn nọmba gidi jẹ nọmba tosoro pẹlu apa báad' to jẹ ọdọ; yun pe nọmba gidi a jẹ bakanna mọ nọmba tosoro a+ìfun apẹrẹ, 3 + 2I je nọmba tosoro, pẹlu apa gidi to je 3 ati apa báad' to je 2..
wikipedia
yo
ti z = a + bí, apá gidi (a) ni a n ṣe àmì rẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀(z), tàbí R(z), bẹ̀ sìni apá pátápátáO' (b) ni a ń ṣe àmì rẹ̀ pẹ̀lú im(z), tàbí I(z)àwọn nọ́mbà tó ṣe rọ́pò, yọkuro, Sodipupọ tàbí ṣepínpín gẹ́gẹ́ bí a ti ń ṣe fún àwọn nọ́mbà gidi, bẹ̀ ni wọ́n sì ní ìdámọ̀ tó lẹ́wà mìíràn..
wikipedia
yo
Fun àpẹrẹ, nọmba gidi nikan ko ni ojuf fun ìdọ́gba Aljẹbra Alápòọńlépupọ (polynomial) pẹlu nọmba àfiṣe gidi (cocient), ṣugbọn awọn nọmba tosoro ni..
wikipedia
yo
(Èyí ni ọ̀pọ̀ àgbàrọ Aljẹbra) (Fundamental theorem of Alge)..
wikipedia
yo
Nínú ìmọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ ìrúyà (báka Engineering), níbi tí í ti dúró fún ìwọ iná (Ele_ Current) àmì tí a ń lò fún ẹyọ GG í ní J, ari bábí pé nígbà míràn nọ́wà tó ṣe kó lé bá bá, a +Al. Bisase nọmba Mathiki ;
wikipedia
yo
Yakubu ti àpèjẹ rẹ n jẹ Jack dan-yumma Gowon ni wọn bi ni kọkàndinlógún oṣù kẹwàá, ọdún 1934 (19-10-1934) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Naijiria lati apá ariwa..
wikipedia
yo
Gowon jẹ́ Ọ̀gágun ni Ilé-iṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ ni ó si tún jẹ́ Olóri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lati ọdún 1966 de 1971..
wikipedia
yo
Ksoro ijoba re naa ni ile Naijiria ja ogun abele lati 1966 si 1971, labe ogagun Odumegwu Ojukwu ti o fe gba ominira lowo ile Naijiria.Awon itọka síàwọn Aare ile Naijiri ogagun ara NaijiriÀwọn oga ọmọṣẹ́ Agbógun Naijiria..
wikipedia
yo
ibíyí ni a bi Obafemi Awolowo si.Ikasí ilu ati Abule ni Ipinle Ogun..
wikipedia
yo
Awujo Haukiro òpìtàn bíi Basil (1981), gbìyànjú láti ṣàlàyé bí àwọn Hausa ti se..
wikipedia
yo
Pataki ohun tí o sọ ní ìṣẹ̀lẹ̀ tí o ṣe ní ìlú kan tí ń jẹ́ Daura..
wikipedia
yo
A gbọ́ pé kànga kan ṣoṣo ló wà nínú ìlú yìí àti pé ejò kan wà ní inú kànga ohun tí kì í jẹ́ kí àwọn ará ìlú pọnmi àyàfi tí ó bá jẹ́ ojo jímọ̀ọ́..
wikipedia
yo
Ìtàn ọ̀hún ṣàlàyé pé àjòjì kan tí ń jẹ́ báyàjid wọ ìlú wa, ó pa ejò yìí..
wikipedia
yo
Ọba ìlú náà tí ó jẹ obinrin sì di iyawo àjòjì ohun..
wikipedia
yo
Ṣé ẹni bá ní ẹrú ni ó ni ẹrú, ẹni fẹ́ ọba ti di ọba..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ pé àwọn ọmọ meje tí ọkunrin ọ̀hún bí ni wọ́n dá àwọn ìsọ̀rí meje ti Hausa ni sílẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n ní àwọn ọmọ meje tí alẹ́ rẹ̀ bí ni wọ́n tẹ ìlú meje yòókù dó..
wikipedia
yo
Méje tó jẹ́ ojúlówó ní ‘Hausa baKwai’ nígbà tí méje yòókù jẹ́ ‘Ban Bkwai
wikipedia
yo
Àwọn Hausa baKwai ni Bram, Daura, Kat, Zaria, Kano, Rano ati Gobir..
wikipedia
yo
Àwọn méje yòókù ni Zamfara, Kebbi, Gwari, Yauri, Nupe, Yorùbá àti Kwarara.Ìtàn ti stride àti ìfẹ́kà (1982) sọ ni a fẹ́ mú lọ nínú iṣẹ́ yìí..
wikipedia
yo
Ìtàn tó wà lókè yìí náà ni wọ́n sọ ṣùgbọ́n wọ́n ṣe àfikún díẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n tọ́ka sí àkọsílẹ̀ kan tí ọjọ́ rẹ̀ ti pẹ́ jọjọ tí ń jẹ́ "Kano Chronicles"
wikipedia
yo
Wọ́n lo àkọsílẹ̀ yìí láti ṣàlàyé pé ọkùnrin kan tí ń jẹ́ ẹ̀ẹ̀wda ni ó kọ́kọ́ jọba ní ìlú Kano..
wikipedia
yo
Wọ́n ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún ọdún sẹ́yìn ni ọba ọ̀hún jẹ (á.D..
wikipedia
yo
Wọ́n ní àkókò yẹn ní ìgbà tí àwọn Hausa bẹ̀rẹ̀ sí kó ara wọn jọ sí abẹ́ àkóso ìlú ṣíṣe.àtúnsọ ìtàn tí wọ́n sọ gbà pé ọmọ báyàji ni gbogbo Hausa ka ara wọn kún..
wikipedia
yo
Ó ṣe àtìpó díẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn ìran kanÚrì (ìpínlẹ̀ Borno)..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó dé ibi kan tí ń jẹ ‘Ram ta gàbas’, ó fi iyawo rẹ̀ sílẹ̀ níbẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ìlú Sanbo (Ìpínlẹ̀ Kano) ó ṣe alábàást àwọn alágbẹ̀dẹ kan tí wọ́n jáfá púpọ̀, wọ́n bá a ṣe ọkọ̀ kan..
wikipedia
yo
A gbọ́ pé ọkọ̀ yìí ni ó lò láti fi pa ẹjọ́ tí ń dààmú àwọn ará ìlú Daura tí o sì fi bẹ́ẹ̀ di ọba wọn..
wikipedia
yo
Ìtàn yìí sọ fún wa pé Gwari ni orúkọ ẹrúbìnrin tí o bí àwọn ọmọ meje tí wọ́n wà ní ìsọ̀rí kejì fún un.Ìtàn yìí tan ìmọ́lẹ̀ díẹ̀ sí ìṣẹ̀dálẹ̀ àwọn Hausa, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìran Hausa ti tàn kálẹ̀ káàkiri àgbáyé àwọn Hausa tí wọ́n jẹ́ onílẹ̀ àti onílé ni apá òkè Ọya ní Orílẹ̀èdè Nàìjíríà ni a ní lọ́kàn nínú iṣẹ́ yìí..
wikipedia
yo
Lára àwọn ìpínlẹ̀ ọ̀hún ni Sokoto, Kat, Zamfara, Kebbi, Kano, Jigawa, Kaduna, Gombe àti Plateau...
wikipedia
yo
O darapọ mọ ẹgbẹ ọmọ ogun Naijiria ni ọdun 1960, ṣugbọn ko lo ju ọdun kan pere to fi kuro to si darapọ mọ ẹgbẹ ori itage kan ti a mọ si Ogunmọla National concert Partyìjòyè
wikipedia
yo
Kò pẹ́ púpọ̀ tí òun pàápàá fi da ère tirẹ̀ sílẹ̀ tí ó sì pè é ní Orlando Owoh and His Omimah bandjárí
wikipedia
yo
Orúkọ àwọn ìyàwó rẹ̀ láti orí ìyàwó àkọ́kọ́ ní Muibatu OriLórígun, Fọláṣadé Akita, Mopelá Ìṣọ̀lá, Deborah akérégbè àti Iyabo Ailorin..
wikipedia
yo
Lára àwọn ọmọ rẹ̀ ni Kayode, Abọ́, Segun, dapọ ati sẹ̀san..
wikipedia
yo
Ó ṣàlàyé pé Orlando fẹ́ràn ẹ̀ṣẹ́ kíkàn àti pé odidi ọdún mẹ́ta ni ó fi jẹ baálẹ̀ àwọn elésèé kíkan nígbà èwe rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó ní ọ̀rẹ́ ní àbúrò òun àti gbajúgbajà olórin tí ń jẹ́ Sunny Ade.alákíkanjú ni Orlando, nípa akitiyan rẹ̀ ni a dá ẹgbẹ́ ìtẹ̀síwájú ìlú ifọ̀n sílẹ̀ (ifọ̀n Progressive Union) ní ọdún 1970..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tó ṣeré ní ìlú owó ní ọdún 1973 ni wọ́n ṣe ètò ìfilọ́lẹ̀ láti kọ́ Gbọ̀ngàn (Town Hall)..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó lè fi ọwọ́ ọ̀tún òhun bọ́ ènìyàn lọ́wọ́ tàbí fi gbé ọmọdé, kò ṣe é mú síbi ìjẹun dáradára..
wikipedia
yo
O ṣalaye pe oun fẹ ki awọn orin ti oun ti ko di kika sori fọ́nrán fidio..
wikipedia
yo
Nínú orin tí ó kọ fún Gbenga Adeboye, ó jẹ́ kí a mọ̀ pé òun sí ni ìyá láyé nítorí pé ó ní òun tí bá Gbenga Adeboye sọ̀rọ̀ pé yóò bá òun sin ìyá òun lọ́jọ́ tí ó bá relé ọ̀gbọ̀.Àwọn ìtọ́ka síÌjápọ̀ lódeàwọn àwo-orin Dr..
wikipedia
yo
Àtòjọ àwọn àagberòrò tí wọ́n jẹ́ ọmọ YORÙ looya àkọ́kọ́ ní ilé Nàíjíríà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Yorùbá..
wikipedia
yo
A kò ọdún tí wọ́n sí òkè orúkọ wọn 1880Christopher Alexander Sapara Williams òun ní ọmọ Nàìjíríà tí ó kọ́kọ́ di looya 1892Rotimi Olùṣọ́mo Alade 1900JohnJohn Augustus ọ̀túnba Payne 1905e.J..
wikipedia
yo
Alexander Taylor 1909John Akinola ọ̀túnba Payne 1910sir Adeyẹ Alakija 1913olayiMika Alakija ithielel K Ladipo Doherty Olase Moore 1921e..
wikipedia
yo
1923Ayodele Williams Steven Bankole Rhodes a.O.D..
wikipedia
yo
CAxton Martins gẹ̀gẹ̀s Adekunle Wright Adegúnlẹ̀ Soẹ̀tàn 1925f.O..
wikipedia
yo
Ẹkùndayọ̀ Kuṣimo sórinola AkinBona sosoadé 1928Samuel Ayodele Thomas Frances edney EUba 1929omosanya Aderd Richard Ade-ẹyọ Doherty Hezent Ajayi Johnson (alias Oníbúwe) Alaba Akerele 1930Abiola Akínwùmí 1931Ogunyemi Ẹ̀bikunle Àjọṣe 1933Oluwọle Ayodele Alakija 1934Adebi Majekoabẹ̀mí 1935st Olaríbigbé Alakija Alakija 1936 Adeṣọ̀gbìn 1940 Adedoyin Ladipo Gabega Gdipo Moore John Idowu CONRed Conred 1942 1942 AdeSegun Wilson Ọdun Moroko Balogun A Fi Taylor Adejumọ Kami Kejumọ fún — Matm Akini Awolowo O. Tuntun A Tuntun O K' A M Kan A * * الس M A Anala Adewe The A' A Oroko A A oni oni La Adeyen Mese ni A Tuntun O Red Ọdun Adeìyàn K A Oroko O tun * Nu Adeyen Me OyO O tun do O Nu Ade Red Red Aderu Red K Red Mo Adewole Adeyen F Oja Bank Adeire Ta Mo D O Pra * Red O tun F Wa M M Awo Red Mo A Nu Wa Wa Aroko O 2016 & O tun do Adeyen O Nu Nu Nu E Mo M E E Red E A M Nu Mo ed E ni E Nu E Tuntun Tuntun O N Wa Red A bu F Fi O O M E Red O tun Red E Red A Pupa O O tun do Ta O Wa Ade O Ọla Tuntun VI
wikipedia
yo
Adio Olayinka Ayoola Abayomi Olowofoku lọ́yà àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ní Williams Alexander sapara Williams..
wikipedia
yo
Ọmọ Yorùbá ni Corsoréètì kìíní ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ní sir Olumúwáwárùrùrùrù..
wikipedia
yo
Òun náà ni ọmọ Nàìjíríà Kìíní tí yóò di adájọ́ ilé-ẹjọ́ Kóòtù gíga (High Court of Judge)..
wikipedia
yo
Ọmọ Yorùbá ni ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí yóò di 'Chief Justice' ilẹ̀ Nàìjíríà ní sir AdéTokunbo Ademola..
wikipedia
yo
Lọ́yà tí ò kọ́kọ́ gba ‘Senior Advo of Nàìjíríà ’Chief f.R.A..
wikipedia
yo
Lọ́yà obìnbin akoko ti o je omo Naijiria ti yoo di adajo ile ejo agba (High Court Judge) ni ile Naijiria ni Mrs Moroko Ọmọ-ẹbọ ti o je omo Akingbẹ̀hìn..
wikipedia
yo
Ọmọ Yorùbá ni.Obìnrin Nàìjíríà tí yóò gba oyè Senior Advo of Nigeria' Nímọ ó ti ó jẹ̀kọ Yorùbá nímọ̀..
wikipedia
yo
OMẸ́Mrs Folake s 'Attorney-General' ti ti yoo jẹ̀kọ Naijiria akọ́mọ'o NaijiriaIle ni Dr di 'President ofko AFIErika tí yoo kó Ilẹ̀wale Elias oun ni Oteshim o Yoruba nimódò International Court of JutylAllah]
wikipedia
yo
O di 'Knight' ni Sokon yóò kọ́ Nàìjíríà tí wọ́lélélé oló Yorùbá nímósì Kitoyí IA
wikipedia
yo
aboard (ADV); nínú ọkọ ojú omi tàbí òfúrufú; the Captain Welcomes you aboard this plane..
wikipedia
yo
Acquit (v) dáláre, dasilẹ the suspect was actationsted by the Court (ilé ẹjọ́ dá arúfin náà sílẹ̀)..
wikipedia
yo
Nigbati o wa papa jẹ Ọba, ibi ti o fi ṣe ibugbe tẹlẹ ni wọn npe ni ile Ato-ọba-tele lónìí..
wikipedia
yo
Ìwádìí tún fi yé mi pé wọ́n máa ńkí àwọn ọmọ bíbí ilẹ̀ yìí báyìí..
wikipedia
yo
ọmọ ládékan, ọmọ amúlé lamúlé orí kó rẹrù, orí Dada pọ̀nponràn..
wikipedia
yo
Èyí ló fà á tí wọ́n fi npe ilẹ̀ yìí ní ari-osùn-pa-ọja..
wikipedia
yo
Ìwádìí tún fi yé mi pé òní ojú ìgbà tí ọ̀mùtí yìí fi únúnmu ọtí..
wikipedia
yo
Wọ́n sì máa nkí àwọn ọmọ bíbí ilẹ̀ yìí ní “ṣàgbà mutí srí mùkọ, ṣa ẹni -rere bátan sá àgbààgbà bárìn, àwa oní bá ẹnití kò sunwọ̀n tán nílé tiwa..
wikipedia
yo
Àwọn alágbẹ̀dẹ ló sì máa ńjẹ “Eji” èyí ló fà á kìkì wọ́n ní "Eji Ara ilagbédè” 🙂
wikipedia
yo
Bi orukọ ile yii se jẹyọ ni yí nipasẹ pipe ilẹ̀ yii ni ejilola leyin olupilẹṣẹ rẹ̀..
wikipedia
yo
Eyi tó fà á ti wọn fi ńpè ni ile Olúkunle nitori igbagbọ àwọn Yorùbá pé “Olú” ni okunrin jẹ ninu ọmọ..
wikipedia
yo
Ẹnití ó kọ́kọ́ dé agbo-ilé yìí ni ìwádìí fi yé mi pé ó njẹ́ búoye..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí olùpilẹ̀ṣẹ̀, wọ́n ní láti máa pe àdúgbò ibití arákùnrin yìí ngbé ní ilẹ̀ ṣẹ̀san ní ìkékúrú..
wikipedia
yo
Èyí ló sì tún fà á tí olùpilẹ̀ṣẹ̀ náà fi fẹ́ràn láti máa jẹ́ ekuru..
wikipedia
yo
ibití ọmọ ọba fúnra rẹ̀ dúrò sì ni a mọ sí Jóta ní ìlú Ií lòní í..
wikipedia
yo
ibití ọba ti tẹ́wọ́gbà á ni à ń pè ní láàkọọ́sìn – ọ̀la-kó-kó-ọ̀sìn..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ńkí àwọn ará àdúgbò yìí pé “Ọmọ ọ̀la tó pọ̀ títí, ọ̀la tí ò ní pẹ̀kun..
wikipedia
yo
Àìsàn ńlá kan ṣe tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ tí wọ́n fi kọ́ ilé ohilẹ̀kùn ńlá kan fún un gẹ́gẹ́ bí ìfà ṣe wí..
wikipedia
yo
Látàrí gbogbo èyí, ìwádìí fi yé mi pé ikú pápá múlò..
wikipedia
yo
Eyi lo fa a ti wọn fi ńpè ile yii ni ile iku-ko-gbo-ilẹkun..
wikipedia
yo
Èyí na fi máa ǹki àwọn ọmọ ilẹ̀ yìí ní "Parakoyi ọ̀gá-ìṣòwò..
wikipedia
yo
Ní àkótán, ìwádìí fi yé mi pé kò sí àdúgbò tàbí agbo-ilé tí orúkọ tó njẹ́ kò ní ìdí.(see Yorùbá Place names)Yorùbá..I..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ yìí ló ṣe wá sí ìlú oyè Ìdí tí wọ́n fi tẹ̀dó sí ìlú oyè ní èyí.Yorùbá..
wikipedia
yo
92.By (Preposition); lẹ̀bàá; My House is by the River..
wikipedia
yo
Ìwọ ìtànná tàbí ìwo iná ní bí apàdé ìtànná ṣe ń sán kiri..
wikipedia
yo
Ẹyọ ìwọ̀n sì fún ìwọ iná ní ampéré (a), tó dọ́gba mọ́ ṣíṣàn kiri Conovob kan agbára iná ní ìṣẹ́jú àáyá.Ìtumọ̀ iye ìwo iná (tí a wọ̀n ní Ampéré) tí ó n gba ọdẹojú (surface) kan kò jà ní iye agbára iná (tí a wọn ní Conovombs) tí ó ń ṣàn kiri l'óde ná láàrín àsìkò kan..
wikipedia
yo
Bákana ìwo ina ti a mo ni ṣiṣan Atanda ninu okun onírin, fun apẹrẹ awon waya opo ina to n gbe ina lati ibikan de ibo miran ati awon waya kekeke ninu awon ero sise (elerẹ̀– ati bi Atanda se n san kọja ninu adènà ina (Resistor), ṣiṣan kiri Ioni (ion) ninu bátìrì (Battery) ati ṣiṣan kiri iho ninu agbeinadiedie (semiwọ̀nyí).Inrinàgbérìn (Eleọ̀gọ̀ọ̀rọ̀4o) Iwọ ina n pese Papa gberin (Magne Field)..
wikipedia
yo
A lè wo pápá gbegberin bíi ọ̀pọ̀ ilá tó yí wáyà po.Ìtọ́kasí ìtànnásayensi..
wikipedia
yo
Iṣẹero onitanna (àbùkù Engineering) ni papa Eko Iṣẹero to un da lori àgbékà ati imulo itanna, Olugbeleoníná ati Iṣẹonigberin oníná..
wikipedia
yo
Pápá ẹ̀kọ́ yí kókó di iṣẹ́ ṣíṣe ní òpin ọ̀rúndún ọ̀kàndínlógún lẹ́yìn ìsọdídùn grabó ìtànná àti ìpèsè agbára onítànna..
wikipedia
yo
lọni ó ti dé ọ̀rọ̀ bí agbára, alájìoníná, àwọn sístemú ìgòÀpótí, Ìgbésẹ̀ Alámiọ̀rọ̀ àti àwọn ìbánisọ̀rọ̀.Ilé onítànnã le tún jẹ mọ́ mọ́ ìṣe oníná..
wikipedia
yo
Iṣẹero onitanna je gbigba pe o da lori awọn iṣoro to je mo awon Sistemu onitanna gbangba bi ifiránṣẹ́ agbara ìtànná ati ikomeric oko, nigbati iseero oníná da lori àgbékà awon síste oníná kekere bi Kọmputa ati awon asoyípo olodídì..
wikipedia
yo
Tàbí, a lè sọ pé àwọn oníṣẹ́ onítànnã ùndá iṣẹ́ wọn lórí lílo ìtànná láti fi fifiránṣẹ́ okùn onítànna, nígbàtí àwọn oníṣẹ́ oníná ùndá iṣẹ́ wọn lórí lílo ìtànná láti ṣe ìgbésẹ̀ àròyé..
wikipedia
yo
loni, ko fi bẹ si iyatọ larin awọn mejeji nitori idagbasoke to ti ba Olusẹoníná agbara.Ẹ tun woiṣẹ́ero Oninaiitọkasi ode odee Global History Network a Wiki-based site with many Resources about the history of íệệe, its members, their professions and àpèjẹ and informational Techologist and Sciences.International EleJákTechnical Commission (i8) Openọ̀gbọ̀se In-ppp Look at Ódi Engineering with Online Courses featuring video Lectures.
wikipedia
yo
Ninu ìmọ̀ Matheki, nọmba báad (imaary number) ni a mọ̀ sí nọmba to ti ti alágbára (square) rẹ jẹ nọmba gidi alápáosi..
wikipedia
yo
Láyé igbana kò sẹ́ni tó gbà pé àwọn nọ́mbà bá hun wá, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe rò pé odò àti nọ́ḿbà apáòsì kò sí tàbí kò wúlò..
wikipedia
yo
Descartes ni ó kọ́kọ́ pè wón bẹ nínú ìwé rè Ìṣirò aláwòni (LA gẹOmerue]] láti fi ré wọn wọn nọ́mbà..
wikipedia
yo
Àmì-ìṣojú fún nọmba ni an pe ní aminomba (145ral)..
wikipedia
yo
Ní èdè ojojúmọ́, a ń lo àwọn aminomba bí àkọlé (fún àpẹrẹ nọ́ḿbà Teliọ̀pá, nọ́ḿbà ilé)..
wikipedia
yo
Ninu imo iṣiro itumọ nọmba ti ṣ'akomo awọn nọmba ọjaati bi ida (fraction), nọmba apaosi (negative), tikónì (Tgainesdental) ati nọmba tosoro (Complex).Awon ọna ìṣèṣirò nọmba bi aropo, ìyọkúrò, ìsọdipupọ, ati iṣẹpínpín ni a n ṢÈWÀdi wọn ninu ẹka imọ iṣiro ti a mọ si Aljẹbra O80 (ABct Algebrab), nibiti a ti n ṢÈWÀdi awọn ọna nọmba ati ẹgbẹ (Group), òrùka (Group (Ring) ati papa (Field).
wikipedia
yo
Onímọ̀ ìṣirò jẹ́ ẹnikẹ́ni tí n ṣe kíkà àti ìwádi nínú pápá ìmọ̀ Ìṣirò.Ìtọ́kasí Mathiki..
wikipedia
yo