cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àwọn ẹ̀rí méjèèjì gbà wípé a bí Jesu Kristi ni Belọ́gánhemu, Judea àti pé ìyá rẹ̀ ni àfẹ́sọ́nà kan, Josẹfu, ẹni tí ó wá láti ìran ọmọnìkejìvídì ọba, tí kò sì ń ṣe baba Jesu.Ìtàn ìbí Jesu ni àwọn Kristẹni fi ṣe ìṣírò ọjọ́ ayẹyẹ Kérésìmesì…
wikipedia
yo
dávídì, gẹ́gẹ́ bí Bíbélì ti sọ ní Ọba kẹta ìjọba àpapọ̀ iṣreali..
wikipedia
yo
àwọn ìwé Sámúẹ́lì sọ nípa ti dávídì pé ó jẹ́ ó dọmọ kùnrin Olùṣọ́ àgùtàn ẹni tí ó gbajúgbajà lẹ́yìn ìgbà tí ó pa Goliati, jagunjagun alágbára ará filistẹni ní is gúúsù àti canani..
wikipedia
yo
Èyí mú kí sáàlu fẹ́ràn Davídì, Davídì sì tún di ọ̀rẹ́ Jonatani ọmọ sáàlu..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n nígbà tí sáàlù wòye pé dávídì le dé ipò ọba, ó gbìyànjú láti pa.,èyí mú kí dávídì ó sá fún èmi tí ó sì fara pamọ́ fún ọ̀pọ̀ ìgbà..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n pa ṣàálù àti Jonatan lójú ogun, a yan dávídì(ẹni tí ó jẹ́ ọmọ ọdún ọgbọ̀n nígbà náà) gẹ́gẹ́ bí ọba gbogbo iṣreali àti Juda.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Goliati (jẹ́ òmìrán kan tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ nínú ìwé Sámúẹ́lì, Bíbélì ṣàpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òmíràn ará Fílístínì kan ti Dávídì ṣẹ́gun lójú ogun...
wikipedia
yo
David Datro Fofaaf (won bi i lọjọ 22 Oṣu kejila ọdun 2002) jẹ agbabọọlu-sise omo orile-ede Ivory Coast ti o n gba bọọlu fun iko ẹgbẹ agbabọọlu-sise Chelsea lórílẹ̀-ede England, bẹẹ naa lo n gba bọọlu fun iko ẹgbẹ agbabọọlu ti orilẹ-ede Ivory Coast.Iṣẹ rẹ gege bi agbabọọlufo bẹrẹ iṣẹ agbabọọlu- rẹ ni Ile-ẹkọ agbabọọlu Afad lorilẹ-ede Ivory Coast, nibẹ ni awọn asawari awọn ọmọ ẹlẹ́bùn agbabọọlu lati orilẹ-ede France, Belgium ati Norway fi ja fitafita lati ra a fun iko agbabọọlu-jẹun wọn..
wikipedia
yo
Kíjo 2,Oṣù Kejì Ọdún 2021, Fako tọwọ́ bọ̀wé àdéhùn ọlọ́dún mẹ́rin pẹ̀lú Ikọ́ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-jẹun ti Rega..
wikipedia
yo
Ninu ifẹsẹwọnsẹ re akoko pelu egbe agbabọọlu-jẹun Molde ninu idije UEFA Europa League, ami-ayo mẹta mẹta ni won gba pelu iko egbe agbabọọlu-jẹun hoffenheim lọjọ 18 osu keji odun 2021, oun ni o gba ami-ayo iríran iko egbe agbabọọlu-jẹun re wole ni iṣẹju mẹ́rìnléláàádọ́rin (74). 28 Osu kejila odun 2022, won kede pe, fọṣan yoo dara po mo egbe agbabọọlu-jẹun Chelsea lọjọ 1 Oṣu January ọdun 2023.Iṣẹ re gege bi agbabọọlu-dije láàarín orile-ede si orile-ede fọṣan kopa ninu idije Orilẹ-ede si Orilẹ-ede akọkọ rẹ pẹlu iko ẹgbẹ agbabọọlu ti Ivory Coast ninu idije Chan 2020 ti won padanu ami-ayo meji si odo ṣowó iko ẹgbẹ agbabọọlu-dije ti orile-ede Niger lọjọ kejidinlogun Oṣu Kẹsan-an ọdun 2019.Awon Àtòjọ iṣẹ rẹ gege bi agbabọọlu-iroyin ẹgbẹ agbabọọlu-iroyin-Asdúdú-Ọlọrun] itọkasi..
wikipedia
yo
Ó wà ní ibùsọ̀ 390 ní àríwá ti Helsinki, olú-ìlú náà..
wikipedia
yo
O fẹ́rẹ̀ tó eniyan 120,000 ńgbé ní Kuopio.Ìtọ́kasí finlánsan..
wikipedia
yo
ààlọ́ oòrùn ati òṣùpaá mí dá lórí oòrùn ati òṣùpaá ooooóo nì ìgbà ìwáṣẹ̀, ọba òde ọ̀run ní ńṣe àpapọ̀ ohun gbogbo, ìkáwọ́ rẹ̀ sì ni gbogbo ohun tí a dá wà..
wikipedia
yo
Ọ̀run ati òṣùpá fẹ́ràn ara wọn gidigidi, tí ó jẹ́ wípé bí òṣùpá ò bá sí nílẹ̀ ọ̀run kọ́ni jẹun àfi ìgbà tí òṣùpá bá dé ,bẹ́ẹ̀ no sì ni òṣùpá bí ọrun kò bá dé kò ní jẹun.Ní ọjọ́ kan ọba òde ọ̀run ránṣẹ́ sí òṣùpá ati ọrun ọmọ rẹ̀ wípé kí wọ́n wá rí òun..
wikipedia
yo
Nígbàtí wọ́n dé bẹ̀, ọba òde ọ̀run sọ fún wọn wípé òhun fẹ́ rin ìrìnàjò kan tí yóò sì pé kí ohun tó padà, òní kí òṣùpá àti ọ̀run lọ fi oríkòrí kí wọ́n ṣe àpérò ẹni tí yóò délẹ̀ dé ohun tí òhun bá wà ní ìrìnàjò..
wikipedia
yo
Wọ́n dúpẹ́ lọ́wọ́ baba wọn, wọ́n sì ṣe ìlérí láti ṣe gẹ́gẹ́ bí baba wọn ti sọ.Ní ọjọ́'rú ọ̀sẹ̀ kannáà, òṣùpá àti ọ̀run fi ojú kàn rà, ṣùgbọ́n oró ó wọ̀ láàrín àwọn méjèèjì lérí ẹni tí yóò délé nígbàtí baba wọn bá lọ..
wikipedia
yo
Igba kúgbà ti ọ̀run àbí òṣùpá bati rántí ìdájọ́ yìí, nínú ọdún wọn a máa sunkún lọ́pọ̀lọpọ̀, ẹkùn wọ̀nyí ni àwa ọmọ ènìyàn npè ni ọjọ́.Èkó inú ààlọ́ ààlọ́ yìí kọ́ wa pé, kí a máa gbà fún ara wa, kí a má máa ṣe èmi jù ọ́, ìwọ jù mi láwùjọ.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
ààlẹ oooo Aaa ayé Àtijọ́, ọrẹ ni ilé àti Ọlọ́run..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ibùgbé wọn jìnà sí ara wọn, àwọn méjèèjì a máa wá ara wọn..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ ìgbà ni Ọlọrun máa ń sọ̀kalẹ̀ láti wá bá ilé ṣeré..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kan, àwọn méjèèjì pinnu láti dé’gbe lọ kí àwọn lè pa ẹran..
wikipedia
yo
Ọlọ́run sọ wípé òun l'ẹ́, nítorí ìdí èyí, òun ni òun yó mú èyí tó pọ̀ níbẹ̀..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ náà fàáké kọ́rí ó ní òun ni àgbà tí ó gbọdọ̀ mú èyí tí ó pọ̀..
wikipedia
yo
Ìjà yìí pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí Ọlọrun fi bínú lọ sí ọ̀run tí ilẹ̀ náà sì bínú lọ..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí olukuluku ti fárígá tí ó sì padà lọ sí ààyè rẹ̀ kí ló wá ṣẹlẹ̀? Òun tó ṣẹlẹ̀ ni pé òjò kò kò rọ̀, àgbàdo pọ́n'gbẹ, kò gb'ọmọ pọ́n, ọmọge lóyún oyún gbé mọ́ wọn lára, akérémọdò w'Ewú ìràwé..
wikipedia
yo
Ìyàn yìí mú títí tí ọpọlọpọ eniyan bẹ̀rẹ̀ síí kú..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ṣe, ọba ìlú wá eéjì kún ẹẹ́ta, ó lo ọ̀kọ̀ aláwọ..
wikipedia
yo
Ohun ti wọ́n yíò ṣe náà ni kí wọ́n gbé ẹbọ lọ sí ọ̀run..
wikipedia
yo
Kò sí ẹni tí ó yọjú láti gbé ẹbọ yìí bí kò ṣe ẹyẹ igún..
wikipedia
yo
Bí igún ti gbé ẹbọ sílẹ̀ tán tí ó ń bọ̀ wá sí ilẹ̀ ayé ní òjò bá bẹ̀rẹ̀ sí rọ̀..
wikipedia
yo
Ọjọ́ yìí l'agbara púpọ̀ tí o fi jẹ́ pé gbogbo àwọn ẹyẹ ni wọ́n ti ilẹ̀kùn ilé wọn mọ́ ori..
wikipedia
yo
Nígbà tí igún dé, ọjọ́ ti gbẹ́ ilé rẹ̀, kò sì rí ibi tí yíò yà sí tàbí f'arapamọ́ sí..
wikipedia
yo
Ohun tí ó tún wá burú ni pé bí ó bá ti fẹ́ ya sí ilé ẹ̀yẹ kan ní ẹ̀yẹ yìí ó ṣàájẹ́ ní orí..
wikipedia
yo
Àwọn ẹyẹ ṣe eléyìí títí orí igún fi pá títí di òní yìí.Èkó inú ààlọ́ ọ̀kánjúwà kò dára..
wikipedia
yo
Kò sí oun ti ó kéré jù fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lati pin bi ìtẹ́lọ́rùn bá wà.
wikipedia
yo
Oore ní igun ṣe, ibi ni wọ́n fi san fún un.àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìjàpá àti àna rẹ̀ àlọ́ oooàlò oooàlò yìí dá lórí ìjàpá àti ana rẹ̀ gbogbo wa ni a ti mọ ìjàpátìrókò ọkọ yánníbo gẹ́gẹ́ bíi ọlọgbọnewe ati ọ̀kánjúà tí ó sì tún jẹ́ tìfunlọ̀ràn.Ní ojo kan ìjàpá gba ilé ana rẹ̀ lọ lọ lọ kí wọ́n..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó dé ilẹ̀ àna rẹ̀, wọ́n ṣe àpọ́nlé rẹ̀ dáadáa..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n bí wọn ṣe ṣe aájò ìjàpá tó, ìwà rẹ̀ kò padà..
wikipedia
yo
Ìjàpá ń ro nínú ara rẹ̀ ọ̀nà tí yíò fi bu díẹ̀ nínú ẹwà náà lọ sí ilé rẹ̀..
wikipedia
yo
Dípò kí ìjàpá tọrọ ẹwà lọ́wọ́ àna rẹ̀, ṣe ni ó ń ro bí yíò ṣe jí nínú ẹwà náà.Ìjàpá wo yanyanyan kò rí ẹnìkankan ni ó bá rápálá lọ sí ibi tí wọ́n ti ń ṣe ẹ̀wà tí ó sì ń hooru yèyẹ..
wikipedia
yo
Ìjàpá bu díẹ̀ nínú ẹ̀wà gbígbóná sí inú fìlà rẹ̀, ó sì dèé m'orí..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ṣe, ẹ̀wà bẹ̀rẹ̀ sí jọ ìjàpá lórí ni ó bá sọ fún àna rẹ̀ pé òún ń lọ sí ilé òun..
wikipedia
yo
Ana ìjàpá sì pinnu láti sinín sí ojú ọ̀nà ìjàpá ro àna rẹ̀ títí kí ó má sin òun ṣùgbọ́n àna rẹ̀ kọ̀ jálẹ̀ pé òun ní láti paá lẹ́sẹ̀ dá.Bí wọ́n ṣe rìn díẹ̀ ni ooru ẹwà bẹ̀rẹ̀ sí jó ìjàpá ní orí..
wikipedia
yo
Ọmọbinrin aláìgbọràn níláti ooooo Gibeah àlọ́ yí dá firigbàgbọ́, ó dá lórí ọmọbinrin aláìgbọràn kan..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn ọmọkùnrin ni ó fẹ́ fi s'aya ṣùgbọ́n kò gbà fún ẹnì kankan nínú wọn..
wikipedia
yo
Àwọn òbí rẹ̀ ní yan ọkọ fún ṣùgbọ́n kò tẹ̀lé ẹnití wọ́n yàn fún un.Ní ọjọ́ kan ó ṣe alápàdé ọmọkùnrin kan tí ó rẹwà, ó sì wú ọmọbìnrin yìí dáadáa..
wikipedia
yo
Ó sọ fún ọmọkunrin yìí pé òun nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, òun sì fẹ́ kí ó jẹ́ ọkọ òun..
wikipedia
yo
Ọmọkùnrin yìí kò pé òun kò ní fẹ́ ọmọbìnrin yìí, ṣùgbọ́n ó fàáké kọ́rí pé ọmọkùnrin yìí ni òun ní láti fẹ́ láìmọ̀ pé ṣènìyàn-ṣẹranko ni ọkùnrin náà, eré inú omi ni, ó paradà láti wá sí Ìjọ àwọn adáríhunrun lásán ni..
wikipedia
yo
Nígbà tí ọmọbinrin yìí kò gbà, ni ọmọkunrin yìí bá sọ pé òun yóo fẹ́ẹ̀, ó sì sọ fún ọmọbinrin náà wí pé ilẹ̀ òun jiná,ọmọbinrin sọ fún un pé ibikíbi tí ọmọkunrin yìí bá ń lọ òun yóo baà lọ..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n rin díẹ̀ tí wọ́n dé ibi tí àwọ̀ ọmọkùnrin yìí wà, ni ọmọkùnrin yìí bá yà sí inú igbó tí ó sì gbé àwo ère rẹ̀ wọ̀..
wikipedia
yo
Ṣé orí tí yóò sunwọ̀n nib'aláwọ̀ rẹ̀ kò ní, ọ̀kan nínú àwọn ọmọkùnrin tí wọ́n ti k’nú sí obìnrin yìí láti fi s'àyà wà lórí ègún tí ó n ṣ'óde..
wikipedia
yo
Bí ó ti gbé ojú wo iwájú ni ó rí èrè tí ó ń gbé ọmọbìnrin yìí mì..
wikipedia
yo
Bí ọkùnrin yìí ṣe ta ìbọn mọ́ eré nìyí tí ẹrẹ̀ sì kú lẹ́yìn èyí ni ọmọbìnrin náà yọ jáde l’ẹ́nu ẹrẹ̀.Èkó inú ààlọ́ ààlọ́ yìí kọ́ wa pé kò yẹ kí a máa ṣe àìgbọ́ràn sí àṣẹ àwọn òbí wa..
wikipedia
yo
ààlọ̀ obinrin kan ati àwọn ọmọ rẹ̀ mẹta ààlọ́ oooo ààlọ́ yí dá fírí, ó dá lórí obinrin kan ati àwọn ọmọ rẹ̀ mẹta.Ní ìlú kan orúkọ ìlú náà ni olówó, obìnrin kan wà tí ó bí ọmọ mẹ́ta..
wikipedia
yo
Oruko awon omo naa ni, wéréwéré laa ségi, arawàrà laa wọ̀gbẹ́ ati Omoniyun ti o je àbígbẹ̀yìn..
wikipedia
yo
Obinrin yìí wà fẹ́ Omoniyún ju àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ lọ, kò sí fi ìfẹ́ yìí pamó fún àwọn ẹ̀gbọ́n Omoniyún..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọjọ́ kan, àwọn ọmọ mẹtẹẹta jáde nílé, wọn kò sì mọ ọ̀nà ilé mọ́..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ṣẹ̀, obinrin yìí bẹ̀rẹ̀ sí wá àwọn ọmọ rẹ̀ pẹlu orin ati omijé lójú..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ṣe, wọ́n taari méjì nínú àwọn ọmọ obìnrin yìí síta..
wikipedia
yo
Inú obìnrin yìí kò dùn torí pé kò rí Omoniyún tiiṣẹ́ àbígbẹ̀yìn ọmọ rẹ̀..
wikipedia
yo
àwọn ènìyàn sì gbìmọ̀ pọ̀ láti dá obìnrin yìí lójú..
wikipedia
yo
Bí obìnrin yìí ti ríi ni ó bú sí ẹkún ni ó tún bẹ̀rẹ̀ sí kọ orín..
wikipedia
yo
Inú ìyá Omoniyún bàjẹ́ gidigidi, o si bẹ̀rẹ̀ sí sunkún lọ si ilé.Ikọ́ inú ààlọ́ àlọ́ yìí kọ́ wá wípé kí a máa fẹ́ràn ọmọ kan ju ọmọ ekeji lọ torí a kò mọ irú ohun tí àwọn ọmọ yìí leè dá ní ọjọ́ ọ̀la..
wikipedia
yo
Òkúta ti ọ̀mọ̀lé kò tún lè padà wá di igun ilé ní ọjọ́ ọ̀la.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Olúróhunbí àti Ìrókò àlọ́ óò ,àlọ́ óò,àlọ́ yìí dá lórí Olúróhunbí àti Olúwèrè ni ayé àtijọ́, obinrin kan wà tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ Olúróhunbí..
wikipedia
yo
Obìnrin yìí kò sì fi inú ṣoyún, bẹ́ẹ̀ ni kò fẹ̀yìn gbọ́mọ pọ́n, èyí jásí pé ó yàgàn..
wikipedia
yo
Dípò kí ó dúró de iṣẹ́ Olodumare, ó gba ọ̀dọ̀ olùwèrè lọ..
wikipedia
yo
Ó ṣe eléyìí nígbà tí ó rí àwọn tí wọ́n jọ wà nínú ipò báyìí tí wọ́n ń gbọ́mọ pọ̀n..
wikipedia
yo
Pẹlu itara ni Olúróhunbí fi jẹ́ ẹ̀jẹ́ pé bi olùwèrè bá fún òun lọ́mọ, òun yio si fún un ni ọmọ naa..
wikipedia
yo
Ẹ̀jẹ̀ yìí jẹ́ ọ̀tún nítorí pé, ewúrẹ́ aguntan ni àwọn obinrin ń pada wá fún olùwèrè gẹ́gẹ́ bí ẹ̀jẹ́.Lóòótọ́, Olúróhunbí lóyún, ó sì bí ọmọbinrin kan tí ó sọ orúkọ rẹ̀ ní àpọ́nbíepo..
wikipedia
yo
Àpọ̀n àpọ̀n ń dàgbà, ìyá rẹ̀ kò sí èranti tí ó bá olú kọ́.Nigba tí tí olú reti Olúróhunbí kí ó wá mú ẹje rẹ̀ ṣe ti kò rí ni oun gan-an bá gbéra ní ọjọ́ kan ó gba ilé Olúróhunbí lọ..
wikipedia
yo
Bí ó ṣe dé’bẹ̀ tí ó f'Ojú kan àpọnbí ni ó bá lé lọ́wọ́ mú tí o sì bẹ̀rẹ̀ sí mú lọ..
wikipedia
yo
ni èkejì ó yẹ kí a máa kó gbogbo àníyàn wa ti Olodumare..
wikipedia
yo
Kí a ma maa fi ìwàǹwára wá nǹkan torí ọba òkè t'ọ́sẹ̀ fun táyé kò gbàgbé Kehinde, ẹ jẹ́ ki a lọ́ra.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ní àwùjọ Yorùbá, ó jẹ́ àṣà àwọn ènìyàn àwùjọ náà láti máa kí ara wọn ní gbogbo àwọn àkókò tí wọ́n bá bá ara wọn..
wikipedia
yo
Yorùbá gbàgbọ́ pé ìkínní jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọ̀nà tí ènìyàn lè gbà láti fi ọmọlúàbí rẹ̀ hàn..
wikipedia
yo
Ni àwùjọ Yorùbá, bi ọmọ bá ji ni àárọ̀, irú ọmọ bẹ́ẹ̀ gbọ́dọ̀ ki àwọn òbi tàbí àwọn àgbàlagbà láàárọ̀..
wikipedia
yo
Bí ó bá jẹ́ pé ọkùnrin ni, irú ọmọkùnrin bẹ́ẹ̀ gbọ́dọ̀ dọ̀bálẹ̀ kí àwọn òbí tàbí àwọn àgbàlagbà..
wikipedia
yo
Tí ó bá jẹ́ pé ọmọbinrin ni, ìkúnlẹ̀ ni yóo fi kí àwọn òbí ati àwọn àgbàlagbà tí ó bá fẹ́ kí.Ohun mìíràn tí ó ṣe pataki láti mọ̀ ni pé kò pọn dandan fún ọmọde láti kọ́kọ́ kí àgbàlagbà..
wikipedia
yo
Bí ó bá jẹ́ pé àgbàlagbà ni ó kọ́kọ́ rí ọmọdé, àgbàlagbà pẹ̀lú lè kí ọmọdé, tí irú ọmọdé bẹ́ẹ̀ yóò sì fi àpọ́nlé tó yẹ fi ìdáhùn sí kíkí náà.Oríṣiríṣi ìkíni ni ó wà ní àwùjọ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ìdí nìyìí tí Yorùbá fi máa ń sọ pé ìkínní ìgbà òjò yàtọ̀ sí ti ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn..
wikipedia
yo
Èyí já sí pé ó ní ọ̀nà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tí a ń gbà láti kí àwọn tí wọ́n ń ṣe iṣẹ́ kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
Ọdún 2023 jẹ́ ọdún tí a wà lọ́wọ́ nínú Kàlẹ́ńdà gírẹ̀rí..
wikipedia
yo
ọjọ́ kẹtàlá sí ọjọ́ Kẹrìnlá oṣù nìkínnijan 13 - Jan 14) – ìpele àkọ́kọ́ tí ìdìbò ààrẹ orílẹ̀-èdè Czech wáyé.
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹ́ẹ̀dógún oṣù kínní(Jan 15)- ọkọ̀ bàlúù kan tí wọ́n ń pè ní yẹtí Airlines Flight 691 jà ní Pokhara, orílẹ̀-èdè Nepal, ó sì pa ó kéré jù, ènìyàn Kandínlãdọ́rin.
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù Kínní(Jan 16) – ọwọ́ ìjọba orílẹ̀-èdè Italy tẹ olórí ẹgbẹ́ jàndùkú kan ti wọ́n ti ún wá fún ọjọ́ pípẹ́, Matteo Messina Devro ní Palermo, Sicily.
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kínní (jan 17) - Nguyen XUan Phù kọ̀wé fiṣẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ orílẹ̀-èdè Vietnam lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwọ́de ìfẹ̀hónúhàn tako àwọn Àìṣedédé ìjọba rẹ̀.Ọjọ́ ogún oṣù Kínní(Jan 20)- àwọn aṣòfin orílẹ̀-èdè Trinidad àti Tobago yan Christine kàngaloo gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ orílẹ̀-èdè náà.
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹẹdọ́gbọ̀n oṣù Kínní(Jan 25)- Chris Hipkins rọ́pò Jakẹfà Aryẹ gẹ́gẹ́ bí Mínísítà Àgbà Orílẹ̀-Èdè New Zealand, ọjọ́ mẹ́fà lẹ́yìn tí Jaàbùmọ́ Aryẹ kọ̀wé fi ipò Mínísítà Àgbà sílẹ̀.
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n sí ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kínní (Jan 27–28) – ìpele kejì ìdìbò Ààrẹ orílẹ̀-èdè Czech ọdún 2023 wáyé, Petr Pavel ni ó jáwé olúborí.Oṣù kejì ọjọ́ karùn oṣù kejì(Feb 5) - ìdìbò Ààrẹ orílẹ̀-èdè Cypriot ti ọdún 2023 wáyé, Nikos Christodouli sì ni ó jáwé olúborí.
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹwá oṣù kejì(Feb 6) – imí-ilẹ̀ Turkey àti Syria bẹ̀rẹ̀, ìmí-ilẹ̀ náà ti pa ó kéré jù ènìyàn ọ̀kànlélógójì ẹgbẹ̀rún ní orílẹ̀-èdè méjèèjì tí ó lé ní ọ̀kẹ́ mẹ́fà ènìyàn ti fara pa.
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹtàlá oṣù Kejì(Feb 13)- ìdìbò sípò Ààrẹ Bangladesh tí ó yẹ kí ó wáyé ní ọjọ́ kàndínlógún oṣù náà wáyé, Shahabubakibuki Chuppù ti ẹgbẹ́ òṣèlú àwàmi League nìkan ni olùdíje ṣipo náà, ó jáwé olúborí nínú ìdìbò náà láì ní alátakò.
wikipedia
yo
Ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejì(Feb 25) - ìdìbò gbogbogbòò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti sílé ìgbìmọ̀ aṣòfin wáyé, Bola Ahmed Tinubu ni ó jáwé olúborí ninu idibo Ààrẹ.Oṣù Kẹtaojo kejìlélógún Oṣù Kẹta(March 18)- idibo sípò àwọn Gómìnà Nàìjíríà àti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àwọn ìpínlẹ̀ tí ọdún 2023 wáyé.O le ka 2023 ní Naijiri ní itọkasi..
wikipedia
yo
Àtòjọ àwọn ìdálẹ̀ 2023 ní orílẹ̀-èdè Nàìgbé ìdálẹ̀ ọjọ́ lọdínlọ Oṣù kejì(Feb 25) - ìdìbò lọ́lẹ̀-èdè Nàíjíríà Nàíjíríà àti sílẹ̀ ìwòmọ̀ Ọba wáyé, Bola Ahmed Tinubu ni ó jawe nínú ìdìbò Aare. elégún ọ̀yẹlé Oṣù kẹta 18 sí ìràji àwọn gominá tí ilé ìgbìmọ̀ àwọn ìpín àwọn ìpínlẹ̀ ti ọdún 2023.Ó tún wáyé ní ọdún àto lè ka àwọn fí ọ̀ṣẹpọ̀ tí ọdún Ọ̀ṣẹẹ̀
wikipedia
yo
Kola Adequette je oloselu omo orile-ede Naijiria, eni ti o je igbakeji gomina ipinle Osun lati osu Kọkànlá odun 2022..
wikipedia
yo
Wọ́n dìbò Adedarapọ̀ gẹ́gẹ́ bí igbákejì Gómìnà Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun nínú ìdìbò yan Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun tí ó wáyé ní ọdún 2022.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ẹyẹ àṣá jẹ́ ẹyẹ tí ó ma ń pa àwọn ẹranko kékèké tàbí ẹja inú omi jẹ gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ..
wikipedia
yo
Àsá je ikan ninu iran awon eye ti awon Geesi n pe ni ACI ACTAE..
wikipedia
yo
Ẹ̀yà àwọn ìran ẹyẹ yí tó 68 tí wọ́npọ̀ sí àwọn agbègbè bíi Eurasíà and Africa..
wikipedia
yo
Yàtò sí àwọn agbègbè tí a mẹ́nubà yí, ẹ̀yà mẹ́rìnlá outside ọ̀tọ̀ ni ó tún wà tí a sì lè rí méjì ní apá North America, nígbà tí a lè rí ẹ̀yà oríṣi mẹ́sànán ní apá Central and South America, àti mẹ́ta ní apá ilẹ̀ Australia.Àṣà kìí ṣe ìran ẹyẹ kan bí kò ṣe gbogbo ẹyẹ tí ó bá ń pa ẹranko tàbí àwọn ẹyẹ ẹgbẹ́ rẹ̀ jẹ.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo