cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
òróró ẹja jẹ́ ìran òróró kan tí wọn má ń rí láti ara àwọn ẹja tí wọ́n lọ́ràá..
wikipedia
yo
Òróró ẹja yí ma ń ní àwọn èròjà aṣaralóore Floyẹ-3 tí ó ma ma ń fún ara ní ọ̀rá tí ó péye..
wikipedia
yo
Lára àwọn aṣaralóore yí ni àkọsílẹ̀ acid (Ẹ̀pà) A, DocosaCHABO| acid (Dha) àti Eirúncooids tí ó stantyn jẹ́ èròjà aláìkọlàpàtàkì tí ó ma ń mú àdínkù bá àrùn jẹjẹrẹ nínú àgọ́ ara ọmọ ènìyàn tí ó sì tún ma ń dẹ́kun àwọn ohun tí wọ́n ma ń ru jẹjẹrẹ sókè ní àgọ́ ara, bákan náà ni ó ma ń mú àlékún bá èròjà Hyperring.”Oorewéwèé nínú ara..
wikipedia
yo
Orísirísi àríyànjiyàn ni ó ti wáyé látẹnu àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ ìlera lórí àǹfàní òróró ẹja nípa ṣíṣe ìwòsàn fún àìsàn ọkàn ..
wikipedia
yo
púpọ̀ nínú wọn ni wọ́n fara mọ́ wípé òróró ẹja ọlọ́ràá dára fún ìwòsàn àìsàn ìdádúró ọkàn.Wọ́n ti ṣe ìwádĩ síwájú sí lórí òróró ẹja ọlọ́ràá àti Òmégà-3 pẹ̀lú agbára rẹ̀ láti ṣe ìwòsàn fún ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn, ìbẹ̀rù, àrùn jẹjẹrẹ, àwọn iṣan ara tó n dáae sílẹ̀ nínú àgọ́ ara, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé wọn kò tí ì wípé fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé òróró sha lè yanjú àwọn ìpèníjà ara tí àti mẹ́nu bà lókè wọ̀nyí..
wikipedia
yo
Àwọn ẹja tí wọ́n jẹ́ ẹja Ọlọ́ràá tí wọ́n ma ń rí èròjà òyì-3 lára wọn yàtọ̀ sí àwọn ẹja tí a ń ṣe jẹ́, bẹ́ẹ̀ sì ní àwọn ẹja tí wọ́n ń ṣòrùn òràkọ̀-3 wọ̀nyí ma ń jẹ ẹwo tó gbé tàbí jẹ́ abẹ́́kọ́ tí wọ́n ní ẹ́ òràẹ̀-3 Fátty acid..
wikipedia
yo
Àwọn ẹja bíi ẹja Shark Bookshop, ẹja tilefish àti ẹja AlBacrin tuna ni won sábà ma ń ní ọrá ògé-3 lára, àmọ́nu látàrí ipò àwọn ẹwo wọ̀nyí nínú ibú omi wọn sábà ma ń jẹ́ àwọn ẹjà tí wọ́n ní máje tí wọ́n pè ní Biomagcation lára nínú omi nínú omi Biomagcation..
wikipedia
yo
Fúndí èyí, àwọn àjọ tí wọ́n ń rí sí ìlera ọmọnìyàn United States Environmental Protection Agency gba gbogbo àwọn obìnrin àwùjọ tí wọ́n ṣì ń ṣabiyamọ ní ìmọ̀ràn láti yẹra fún jíjẹ́ irúfẹ́ àwọn Ẹja bẹ́ẹ̀ ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà nítorí àpọ̀jù àwọn májèlé bí Méjẹ̀ Tisọdá tí ó pọ̀ ní ara àwọn Májẹ̀mú tí a ti mẹ́nu bà ṣáájú..
wikipedia
yo
Àmọ́ ní nkan bí ọdún 2019, àjò Food and Drug Administration (FDA) fowo sí àwọn oògùn kan bíi yíjúza, Oktry (òò-3 acid ezion esters), Vascepa (E] crin acid), pẹ̀lú Epanova (Omega-3 carboxylic ríran)..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí òògùn àtọwọ́dá tí ó dára tí wọ́n pèsè gẹ́gẹ́ bí òróró ẹja àgbélẹ̀rọ tí ó sì ni àwọn èròjà ásíìdì tí ó wúlò fún ara.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Lionel Andrés Mes (tí a tún mọ̀ sí Leo Messi) jẹ́ ògbólógbòó agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Argentina tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Paris Saint-Germain.History gba ìfi ẹ̀yẹ Ballon d'Or gẹ́gẹ́ bi agbábọ́ọ̀lù tí ó dára jùlọ ní gbogbo àgbáyé fún ìgbà keje ní ọdún 2021, eleyi mú fi méjì jù ti Cdẹ́biano Ronaldo tí ó jẹ́ akọjú rẹ̀ lọ.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Òróró jẹ́ ohun èlò kan tí ó gbajúmọ̀ tí wọ́n jẹ́ kẹ́míkà tí wọ́n ṣe láti ara hydrocarbons tí ó sì tún jẹ́ Hydtapho tí wọn kò fi omi sínú rẹ̀ rárá..
wikipedia
yo
A lè lo irúfẹ́ òróró míràn fún àwọn ohun èlò èrò ilé wa bíi ọkọ̀, alùpùpù àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
A lè lo àwọn òróró bí mineral oil fún ìtọ́jú àwọn aláárẹ̀ nílé ìwòsàn, bẹ́ẹ̀ ni àwọn òróró kan wà tí àwọn ẹlẹ́sìn ma ń lò lọ́nà ọ̀tọ̀ láti fi ṣe àdúrà tàbí ìyàsímímọ́ nínú ẹ̀sìn wọn.Fún ìpèsè oúnjẹ oríṣiríṣi àwọn òróró ni ó wà fún jíjẹ, yálà èyí tí wọ́n yọ láti ara èwe ni tàbí ẹranko, tí wọ́n sì ń lòó fún Ìpèsè Oríṣiríṣi oúnjẹ jíjẹ́ ní àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé gbogbo..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà ni wọ́n ma ń fi òróró dín àwọn oúnjẹ kan nítorí ó dára jù kí wọ́n fi omi lásán ṣe wọ́n lọ..
wikipedia
yo
Àwọn èyí tí à ń lò láti fi pa irun ni ó má ń jẹ́ kí irun wa ó dúdú kí ó sì má dán yóò yóò ti kọ́ fi ní ta kókó.Fún ìjọsìn oríṣiríṣi ọ̀nà ni ọmọnìyàn ti lo òróró gẹ́gẹ́ bí ohun ìyàsí mímọ́ fún ìjọsìn nínú ìtàn lórílẹ̀ àgbáyé..
wikipedia
yo
Pupọ àwọn eniyan ni wọ́n kàá kún ọ̀nà kan pataki tí wọ́n fi lè mú ìdàgbàsókè bá ẹ̀mí ninu ìjọ́sìn wọn..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ ni ẹ̀sìn Judaism.[ àti ẹ̀sìn Christianity.Fún àmótútù àwọn òróró kan wà tí wọ́n jẹ àmótútù, bíi àpẹẹrẹ ẹ̀rọ tí ń kúá wá transmers..
wikipedia
yo
Àwọn òróró tí wọ́n ń lò fún mímú nkan tútù yí ni wọ́n ma ń dẹ́kun ìgbóná-gboòru tí ó ma ń ṣẹlẹ̀ látàrí iṣẹ́ tí àwọn ẹ̀rọ náà ń ṣe.Ẹ tún le wọ eṣíṣẹ́lent, kẹ́míkà tí wọ́n ń lò láti jẹ́ kí omi àti epo tàbí òróró dà pọ̀.Àwọn ìtọ́ka síìtàkùn ìjásóde Petroleum Online e-learning Resource from Irdrd Chemical sub”.
wikipedia
yo
Yunifásítì Adekunle Ajasin, Akun-akoko (aaua) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Yunifásítì ìjọba ìpínlẹ̀ Òndó..
wikipedia
yo
Yunifásítì náà wà ní Aàkún àkókò, ìpínlẹ̀ Òǹdó, Nàìjíríà.Ìtàn ìjọba ìpínlẹ̀ Òǹdó kọ́kọ́ dá Yunifásítì Adékúnlé Ajasin kalẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ní ọdún 1982, adarí Yunifásítì náà nígbà yẹn ni Olóyè Michael Adékúnlé Ajasin..
wikipedia
yo
Ijoba ologun ti o tele yi oruko Yunifasiti naa da si Yunifasiti ipinle Ondo ni odun 1985.Awon itọkasi Adekunle Ajasin..
wikipedia
yo
Oko tàbí mọ́tọ̀ (ni ó wá láti inú èdè ) ni ó jẹ́ èrò tí ó ń gbé ènìyàn tàbí ẹrù láti ibìkan sí ibòmíràn..
wikipedia
yo
Ọkọ̀ lè jẹ́ kẹ̀kẹ́ alùpùpù, kẹ̀kẹ́, ọkọ̀ àjàgbé, rélùwéè, ọkọ̀ ojú-omi, ọkọ̀ akérò, ọkọ̀ akérò ojú-omi, ọkọ̀ òfurufú , bàlúù àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn ọkọ̀ arinlẹ̀ ni a pín sí àwọn ọkọ̀ tí wọ́n ń lo ipa tí s mọ̀ sí (Force) láti fi lé kúrò ní ojú kan sí òmíràn Webtore.Ani.org sọkún>àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
rélùwéè tí a tún mọ̀ sí ọkọ̀ ojú-irin jẹ́ ọ̀nà kan pàtàkì tí ọmọnìyàn nínú rẹ̀ láti fi má sẹ́rìnàjò láti ibi kan sí òmíràn..
wikipedia
yo
Ìyàtọ̀ rélùwéè sí oko tẹ́gèépópó ni wípé kìí rìn lójú títì tí a tẹ́ pẹrẹsẹ, àyà fi ojú irin tí a ti tò kalẹ̀ láti ibìkan sí ibòmíràn àwọn irin tí wọ́n tò kalẹ̀ kí ọkọ̀ ojú-ìrìrn yí ń gba ní kìí fi bẹ́ẹ̀ ń mú ìnira dání pẹ̀lú lílọ bíbọ̀ ọkọ̀ náà lórí ìrìn..
wikipedia
yo
Ilé-iṣé ọkọ ojú-ìrìrn ni ó ń sẹ̀ alámójútó gbọkehùn ìrìnà ọkọ ojú-irin..
wikipedia
yo
Ọkọ̀ ojú-irin yí ni ó ma ń lo iná mana-mana, epo Dict tabi kí wọ́n lọ kó láti lè jẹ oko náà ó gbéra láti ibìkan sí òmíràn..
wikipedia
yo
Púpọ̀ àwọn ojú-irin ti ọkọ̀ yí ń gbà má ń sábà alámì tó ń dúró bí màjàlà fún àwọn adarí ọkọ̀ rélùwé náà..
wikipedia
yo
Ọkọ̀ rélùwéè fini lọ́kàn balẹ̀ bí a bá ń sọ nípa ìrìnà ọkọ́..
wikipedia
yo
ọkọ̀ ojú ìrírí ní agbára láti kọ́ èrò tó pọ̀ gidi lásìkò kan náà, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé kò fi bẹ́ẹ̀ rọrùn láti lò, ó sì gbówó lórí yàtọ̀ sí àwọn ọkọ̀ tókù.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Ẹran jẹ́ orúkọ gbogbo gbọ́ fún ẹran tí a lè rí lára ara ẹran yálà ti ewúrẹ́ tàbí ti màlúù.Nígbà láé láé, àwọn ọmọ ènìyàn ma ń dédé àwọn ẹranko láti pa wọ́n fún jíjẹ, àmọ́ nígbà tí ó yá wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ń rẹ̀ tàbí sìn wọ́n gẹ́gẹ́ bí ohun ọ̀sìn ní ilẹ̀ tí wọ́n sì ma ń mú wọn pajẹ nígbà tí àyè rẹ̀ bá ṣí sílẹ̀..
wikipedia
yo
Lágbàáyé lónì, ẹran màlúù ni àwọn ènìyàn ń jẹ jùlọ ní gbogbo àgbáyé, lẹ́yìn náà ni ó kan ẹran ẹlẹ́dẹ̀ àti ẹran adìyẹ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, Brazil àti China ni wọ́n jẹ́ orílẹ̀-èdè tí wọ́n ń pèsè ẹran yí jùlọ..
wikipedia
yo
Wọ́n le lo ẹran màlúù ní oríṣiríṣi ọ̀nà; wọ́n le gé wẹ́wẹ́, tàbí kí wọ́n sin sínú pẹpẹ kí wọ́n fi ṣe súyà, wọ́n le lòó kí wọ́n fi ṣe meetpie àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Bí a bá jẹ́ ẹran lálá jù, ó lè fà kí àrùn jẹjẹrẹ inú ẹ̀mọ̀ àti àìsàn ọkàn ó mú ní paá paá jùlọ bí wọ́n bá ti fi àwọn kẹ́míkà kan kun láti lè jẹ́ kí ó ma ń bàjẹ́.àwọn àìka sí ìlọ..
wikipedia
yo
Adìyẹ (Gallus Gallus domesticus) jẹ́ ẹ̀yà ẹyẹ àti ẹranko ilẹ̀ tí à ń sìn ní ilẹ̀ tí wọ́n sì pín sí ẹ̀yà oríṣiríṣi bíi; Grey and the Ceylon junglect tí a le rí ní apá southeastern àsíá..
wikipedia
yo
A lé akọ adìyẹ ní akọ tàbí kí a pèé ní àkùkọ yálà èyí tí ó ti dàgbà tàbí èyí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń dàgbà bọ̀..
wikipedia
yo
èyí tí ó jẹ́ abo ni a lè pè ní abo adìyẹ tàbí obì yálà èyí tí ó ti dàgbà tàbí èyí tí ó n dàgbà bọ̀..
wikipedia
yo
Ìran ọmọnìyàn ń sin adìyẹ yálà abo tàbí akọ gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ yálà nípa jíjẹ ẹrán wọn tàbí jíjẹ ẹyin tí wọn bá yẹ̀ sílẹ̀.Nínú gbogbo ẹranko tàbí ẹyẹ oko tàbí ilẹ̀, adìyẹ ni wọ́n sábà ma ń sìn jù gẹ́gẹ́ bí ohun ọ̀sìn jùlọ pẹ̀lú iye rẹ̀ ti tó 23.7 bilionu , tí ó sì tún gbéra sọ sí bílíọ̀nù mọ́kàndínlógún (19) ní ọdún 2011..
wikipedia
yo
wọn an pé akọ adìyẹ tí wọ́n ti tẹ̀ lọ́dàá ni Cpọ̀n Wọn ń pe adìyẹ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ n dàgbà ní chick Wọ́n n pe akọ adìyẹ''' tí kò tíì ísan kan ní Amúṣan _*wọ́n n pè obì díye ti ìyá àti bàbá rẹ̀ kìí ṣe ẹ̀yà kan náà ni GGlll Fowye.
wikipedia
yo
Wọ́n an pé abo adìyẹ tí kò tíì pé ọdún kan ní Pulet’’bí wọ́n ṣe rí àti ibùgbé wọn Àwọn adìyẹ jẹ́ ẹ̀yà ẹranko jewe Nígbàkigbà (ọmòdodo)..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà, wọ́n má ń fẹsẹ̀ walẹ̀ tàbí tanlẹ̀ láti wá hóró èso, kòkòrò gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ tó fi mọ́ pípa àwọn ẹranko ilẹ̀ bí aláǹgbá ọmọ eku tàbí ọmọ àṣẹ̀ṣẹ̀ pa ejò fún jíjẹ..
wikipedia
yo
Adìyẹ ní àǹfàní láti lò tó ọdún márùún sí mẹ́wá láyé, èyí tó dàgbà jùlọ gẹ́gẹ́ bí àwọn Guinness World Records..
wikipedia
yo
ti sọ ni ó lo ọdún mẹ́rìndínlọsọ́nàa lè ṣe àdáyanrí akọ adìyẹ yàtọ̀ sí abo adìyẹ pẹ̀lú ìtí ìdí wọn tó má ń pọ̀ Òrub-orób àti iye ọrun wọn tó má ń rí jọ̀bọ̀tọ̀-jọ̀bọ̀tọ̀ àti bí ara wọn ṣe má ń dá yinrin yinrin ju ti obìdíye lọ..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé nínú àwọn ẹ̀yà àwọn adìyẹ míràn, iye ọrun akọ adìyẹ nìkan àti ọrùn rẹ̀ tí ó ma ń rí ṣooro sókè ni ó fi ma ń yàtọ̀ sí abo adìyẹ..
wikipedia
yo
A tún lè lo ìrísí ẹsẹ̀ àti ìgànẹsẹ̀ wọn láti fi ṣe ìyàtọ̀ láàrín takọ-tabo adìyẹ tí a ń sọ yí..
wikipedia
yo
Bákan náà ni a lè fi ọgbẹ́ orí àkùkọ dá wọn mọ̀ yàtọ̀ sí abo adìyẹ..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà ni àwọn akọ adìyẹ kọ̀ọ̀kan ma ń hu irun tàbí ìyẹ́ ní abẹ́ ojú wọn látàrí àwọn oògùn àti abẹ́rẹ́ tí wọ́n bá ti fún wọn kí wọ́n lè dàgbàgbà yàtọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn adìyẹ ilẹ̀ kò fi bẹ́ẹ̀ ni anfani láti fò lọ títí, wọn kò lè fò sórí àmù, odi, ati inú igbó tí wọn yóo ti ní anfani láti jẹ..
wikipedia
yo
Wọ́n lè fò fẹ́rẹ̀ láti gbafẹ́ nínú àdúgbò wọn tàbí kí wọ́n fò pìrìrì nígbà tí wọ́n kéfin ẹ̀wù kan tàbí òmíràn.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Ẹ̀yin ni a lè pè ní apó-Luke tómi-jẹ̀jẹ̀ tí ó dara pọ̀ mọ́ra wọn tí ó ń di òròmọdìyẹ nígbà tí ó bá ti tó àsìkò rẹ̀..
wikipedia
yo
púpọ̀ àwọn kòkòrò tí wọ́n jẹ́ elégungun lẹ́yìn yàtọ̀ sí ènìyàn ni wọ́n sábà ma n sábà yé ẹ̀yìn àwọn ẹranko fáfá bí ejò tàbí òní àti ẹyẹ a máa yé ẹ̀yìn tiwọn sórí ọ̀dàn, wọn kìí yè sínú [[om.[
wikipedia
yo
Ìrísí àwọn yín wọn ma ń yàtọ̀ síra wọn, àmọ́ gbogbo ẹ̀yin wọn ló má ń lépo lára..
wikipedia
yo
Yálà ẹ̀yin náà nípọn kò nípò, gbogbo ìbíntì àwọn ẹranko wọ̀nyí yóò bá yé ẹ̀yìn sí lórí ọ̀dàn, ibẹ̀ gbọdọ̀ má lọ́wọ́rò tí yóò sìkò dàgbà sí..
wikipedia
yo
Bí ẹ̀yin náà bá ti wá gbọ́ dáa dáa, ẹranko inú ẹ̀yin náà yóó fọ ẹ̀yin náà jáde..
wikipedia
yo
Ẹ̀yin tí ó tóbi jùlọ nínú àwọn ẹ̀yin ní ẹ̀yin ẹja whale Shark tí ó tó ìwọ̀n ..
wikipedia
yo
ẹja whale Shark kìí ye ẹyin tirẹ̀ nítorí kìí ṣe ẹja jomi-jòkè, inú rẹ̀ ni ó tí ún pa ọmọ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ẹyin ẹyẹ ògòǹgò tí ẹyin tirẹ̀ tọ̀ àti , jẹ ẹyin ẹyẹ tí ó tóbi jùlọ ní gbogbo àgbáyé,.ẹyẹ Aṣọso ni ẹ̀yin rẹ̀ kéré jùlọ ní àgbáyé, tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ 6.35-11.4 17metres (0.250-0.449 in)..
wikipedia
yo
Ẹyin ti àwọn ẹranko afàyàfà, ẹja, kòkòrò àti àwọn eranko tíkò légungun ma n yẹ kéré jùlọ sí ti aṣọso.àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àyìnlá jẹ́ fíìmù àgbéléwò olókìkí ajẹmórin kan tí ó dá lórí ìtàn ìgbésí aye Àyìnlá Yusuf tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àyìnlá Ọmọwúrà, olórin Àpàlà tí má rẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Báyéwù gún pa nínú ìjà ilé ọtí ní Ọjọ́ 6, Oṣù Èbìbí, Ọdún 1980 ní ìlú Abẹ́òkúta..
wikipedia
yo
Fiimu naa jẹ ṣifihan ni ọjọ 13, oṣu Okudu ọdun 2021 ni Ilu Eko, a si gbe e jade ni awọn ile iṣafihan ere ni ọjọ 18, oṣu kẹfa, ọdun 2021..
wikipedia
yo
Fíìmù náà jẹ́ yíyà pẹ̀lú ìyeye bí ìlú Abẹ́òkúta, tí wọ́n yá ní ní Abeokuta, Ìpínlẹ̀ Ògùn ṣe rí ní àwọn ọdún 1970 àti ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 1980..
wikipedia
yo
Lateef Adedimeji ni o kopa gege bi Àyìnlá, pẹlu awọn oṣere bii Omowumi Dada, Bimbo Manuel, Ade Laoye, Kunle Afolayan, Bimbo Ademoye and Mr Macaroni ..
wikipedia
yo
Àyìnlá ní fíìmù àgbéléwò pàtàkì àkọ́kọ́ Kelani láti ìgbà tí ó ti gbé Dazzling Mirage jáde ní ọdún 2015..
wikipedia
yo
Ètò ìṣúná fún fíìmù àgbéléwò yìí jẹ́ gbígbé jáde gẹ́gẹ́ bí (àádọ́ta Milionu)..
wikipedia
yo
N50 million.Ẹda-itan Lateef Adedimeji bíi Àyìnlá Omowumi Dada Bimbo Manuel Ade Laoye bii Jayé Kunle Afolayan bíi Àjàlá Bimbo Ademoye Mr Macaroni bíi bayéwu ami-eye Awọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Eré ìdárayá ni a lè pè ní ìfigagbága tí a ń fi gbogbo ara ṣe nípọn níbi eré ni tàbí ìdíje..
wikipedia
yo
Tí a fi ń mú aláfíà ara le koko tàbí kí a lòó láti fi níjọ́ nípa irúfẹ́ eré ìdárayá bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọjọ́ọ́ ẹni tí a sì tún fi ń ṣe ohun ìgbádùn fún àwọn òńwòran..
wikipedia
yo
Eré ìdárayá sí le jẹ́bọ́hùn tí a gbé kalẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ètò ẹlẹ́sẹ̀ẹsẹ̀ léte àti le jẹ́ kí ara ó le koko..
wikipedia
yo
Onírúurú eré ìdárayá ló wà láti bẹ̀rẹ̀ láti orí ẹnìkan sí meji tabi èléeniyan pupọ tí wọ́n lè pín sí ikọ̀ ati ìsọ̀rí ìsọ̀rí..
wikipedia
yo
Àwọn akópa nínú eré ìdárayá lè díje láàrín ara wọn kí apá kan ó sì gbégbá orókè lẹ́yìn ìdíje náà..
wikipedia
yo
Bákan náà ni àwọn igún meji tí wọn ń díje ninu eré ìdárayá lè ta omi ní èyí tí kò ní sí ẹni tí yóo borí..
wikipedia
yo
wọn lè gbé eré ìdárayá onídíje kalẹ̀ láti ma fi mú olùborí lẹ́yìn ìdíje..
wikipedia
yo
Onírúurú eré ìdárayá ni àwọn eniyan ma ń ṣe lọdọọdun tí ó sì ma ń mú ifẹsẹwọnsẹ dání..
wikipedia
yo
Ìdíje eré ìdárayá ni a mọ̀ sí àgbékalẹ̀ oríṣiríṣi ayọ̀ tí ó ní ṣe pẹ̀lú ìgbéra kan kan nígbà tí a ń díje lórí àmì-ẹ̀yẹ kan lábẹ́ ìṣàkóso adarí irúfẹ́ ìdíj eré ìdárayá bẹ́ẹ̀.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Janet febisola Adéyẹmí (ọjọ́ ìbí jẹ́ oṣù kẹjọ ọdún 1958) jẹ́ ààrẹ tí ó wà ní pọ̀ lékè fún àwọn obìnrin tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ mining ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Ṣóto fún àwọn oníṣẹ́ mining ní ilẹ̀ òkèrè..
wikipedia
yo
Ó ṣiṣẹ́ lábẹ àwọn ìgbìmọ̀ fún Gómìnà tí wọ́n yàn ní ìpínlẹ̀ Òndó tí wọ́n pè ní strategic Development and Policy implementation ní ọdún 2016..
wikipedia
yo
ó wà lára àwọn ẹgbẹ́ Albàá fún Civil Society Network Cooration and InterIrúgbìn nípa ti iṣẹlẹ ti o ṣẹlẹ ni Ipinle Kaduna..
wikipedia
yo
Ó ti ṣiṣẹ́ takuntakun ní ilé àwọn aṣòfin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ICCRC, ó tún jẹ́ Senior Special Assistant sí Ààrẹ níbí kà gbìmọ̀ ọ̀rọ̀ ní ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin, ó jẹ́ alága fún ẹgbẹ́ iṣẹ́ kókó ní ìpínlẹ̀ Òndó, àti àwọn iṣẹ́ mìíràn tí ó jẹ mọ́ ìlọsíwájú.Nígbà tí o ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin, ó jẹ́ alága fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Irri, Flood and èròSion Control àti igbá kejì alága ẹgbẹ́ Solid Tá7VIn and Water Resources..
wikipedia
yo
ó jẹ́ onígbọ̀wọ́ fún àwọn ohun tí ó bá òfin mu lára, nígbà náà ni ó ń ṣe iṣẹ́ fún àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú kékèké..
wikipedia
yo
Ni osu kesan ni odun 2018, o pinu lati gbe igba fun ipo Senato ni Ipinle Ondo labẹ egbe oselu All Progressive Congress (APC).Iroko ìgbé ayé ati àwọn ẹbí rẹ̀Janet Adeyemi je ọmọ bibi Oloye Ebenezer Akinjiye Adepoju ati Oloye agbaỌmọọba Florence Moroko Moroko ti won pe ni yata ti ile oluji ni Ipinle Ondo..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀, Olóyè Adépọ̀jù jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba tí ó ń ṣe àyẹ̀wò lóri àwọn tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ lórí òpópó-ọ̀nà tí ó Wọnú ilé Olúji..
wikipedia
yo
Nígbà tí ìyáa rẹ̀ tí ó jẹ́ olóyè àgbà jẹ́ oníṣòwò tí ó yanrantí tí ó jáde láti ìdílé kan tí ó dáńtọ́, nípasẹ̀ èyí ni ó fi di oníṣòwò ti ayé mọ́ ní ìlú rẹ̀..
wikipedia
yo
Lara awon molebi re, oba(Engr.) Stephen SUlae Adedùgbẹ̀ jẹ́ Ọba tí ó wàjà ní ilé olú tí ó jẹ́ ẹni kan tí ó nípa gboogi ni gbogbo ile Koodo-ọ-jíire orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, The jegun of ile-ì.O dagba ni ìpínlẹ̀ jọ nuosi nígbà oògùn kan gbogbo àwọn bíbí àwọn fẹ́ rẹ̀ fẹ́ wọn tan nígbà náà, ṣùgbọ́n ara-ilé rẹ̀ kan ni ó ṣe ní ó ṣe sá kúrò nínú ìpínlẹ̀ náà bóbí ìlú tí wọ́n bí sí sí sí sí sí sí ìlú tí wọ́n nlò lati ọmọ (ví kan bí pẹ̀lú ọmọ ti wọ́n bí ó lọ́wọ́ * gbogbo * * gbogbo tí ó gba ìyẹ ní gbogbo pẹ̀lú ọdún kan gbogbo gbogbo tí wọ́n gba gbogbo pẹ̀lú ara rẹ̀, ṣùgbọ́n ara lati ó gba lati ṣụ̀̀ ní ìpínlẹ̀ náà sí ìpín kan * ti sí ìlú kan sí wọ́n bí sí gbogbo ilé rẹ̀- ] Ní ó ṣe ní ó jẹ́ ti ilé rẹ̀ pé ìyà ní ìpínlẹ̀ rẹ̀ lára gbogbo kan gbogbo àwọn bí àwọn ọmọ kan ni ilé rẹ̀ ni ìpínlẹ̀ rẹ̀ ní ó maa ti o maa ti o pé sí ọdún kan tí ó maa ka gbogbo rẹ̀ kan tí gbogbo kan ni gbogbo rẹ̀ ni ilé-ì rẹ̀ tí wọ́n ti maa oògùn gbogbo àwọn pé àwọn tí wọ́n bí
wikipedia
yo
Adéyẹmí kàwé ní Fásitì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ní ilẹ̀ ìfẹ́ láti gboyè nínú ẹ̀kọ́ Gology..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó kàwé tán, ó sin ìjọba gẹ́gẹ́ bi akẹ́kọ̀ọ́ géology..
wikipedia
yo
adébọ̀wálé "Débọ̀" Adédayo (tí a bí ní ọjọ́ kẹta, Oṣù karùn-ún, Ọdún 1993), tí orúkọ ìnagí rẹ̀ jẹ́ Mr Macaroni, jẹ́ òṣèré orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, apanilẹ́rìn-ín, afẹ̀rọhan-ẹ̀rọ-ayé-Blujára àti Aja-tọ̀ọ́- ní-Lọ-
wikipedia
yo
Ó kọ́ bí a ṣe ń pani lẹ́rìn-ín, ó sì di gbajúmọ̀ látàrí àwọn fọ́nrán kékèèké rẹ̀ tó ti máa ń fi ara rẹ̀ hàn gẹ́gẹ́ bíi olóṣèlú kan tó lówó, tó sì fẹ́ máa fẹ́ àwọn ọdọmọbinrin, nínú àwọn eré yìí, orúkọ rẹ̀ máa ń jẹ́ “Oore wá”
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ ènìyàn mo Débọ̀ látàrí “O", “reaki frearea ati “You Are Alaya Well” tó máa ń sọ ní gbogbo ìgbà nínú àwọn fọ́nrán rẹ̀.Àtòjọ àwọn fíìmù àgbéléwò rẹ̀:Àwọn eré orí amóhùnmáwòrán Àwọn àmì-ẹ̀yẹ Wkò Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Eyi ni atojo awon fiimu Naijiria ti won se jade ni odun 2023.odun 2023osu kinni si osu ketaosu kerin si osu kefaosu keje si osu Kesanosu kewa si osu kejìlàáwon itọkasi..
wikipedia
yo
Ade Laoye jẹ́ òṣèrébìnrin láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Pennsylvania State University, níbi tí ó ti kọ́ nípa eré orí-ìtàgé.Ade Laoye kọ́kọ́ hàn sí gbàgede nínu fíìmù àgbéléwò knofẹ́lẹ́ on Heaven's door láti ọwọ́ Emem Isong..
wikipedia
yo
Ade tun han ninu Lunchtime Heroes lati ọwọ́ Seyi BabaTope ati ninu fiimu kéékèèké ori Africa Magic, ti àkọ́lé rẹ̀ n jẹ́ Hush láti ọwọ́ oyè Agúnbíadé..
wikipedia
yo
Ade Laoye pẹ̀lú àwọn ògbóǹtarìgì àwọn òṣèrébìnrin mìíràn bíi Kehinde Bankole, Munachi Abia, àti Omowumi Dada, ni Tunde Lrù fi han pe wọ́n jẹ́ olú ẹda-itan ninu fiimu àgbéléwò Finding Hubby..
wikipedia
yo
Wọ́n yan Ade Laoye fún àmì-ẹ̀yẹ ti Barrymore Award fun orin kan tí ó kọ ní ilé-iṣẹ́ The Arden Theatre.Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀ a Naija Christmas (2021) Collision course (2021 film) (2021) Finding Hubby (2020) Lizard (2020) a Second Husband (2020) Walking with Shadows (2019) Ọ̀gá John (2019) Knockout Blessing (2018) Castle & Castle (2018) You Me Maybe (2017) Hush (2016) erased (2015) Lunch Time (2015) Dowry (2014) Àyìnlá (Fiimu àgbéléwò)Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìmọ̀ AÁYAN-ògbufọ̀ jẹ́ ìmọ̀ iṣẹ́ alakadá tí ó kó ọ̀pọ̀ owó pọ̀ tí ó sí ń dojú kọ lílò ètò TÍỌ́RÌ, àpéjúwe àti àiṣts igbuon sise, Tapita, àti isodò..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀ka ìmọ̀ ọlọ́pọ̀ ẹ̀ka, aáyan-ògbufọ̀ ṣe ọ̀pọ̀ ìmọ̀ láti inú àwọn ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ tí wọ́n ṣe ìrànwọ́ fún aáyan-ògbufọ̀..
wikipedia
yo
Lára àwọn wọ̀nyí ni ìmọ̀ ìsàfíwéra lítíréṣọ̀, ìmọ̀ Sayẹn Kọ̀m̀ta, Imọ-Ìtàn, Imọ Ẹ̀dá-Èdè, Imọ ajọṣepọ Èdè, Imọdoye, Imọ Ìfara-Soba, ati IỌ̀dọ́de.Èdè Ìperí yii “Translation Studies” jẹ́ èyí tí onímọ̀ ọmọ ilẹ̀ America tí ó Amsterdam ṣe ibùjókòó ní James S..
wikipedia
yo
Holmes fi lọ́lẹ̀ nínú bébà akadá rẹ̀ ti ọdún 1972 "The name and nature of translation studies", eyi ti o di itẹwọgba gẹ́gẹ́ bi ọ̀pákùtẹ̀lẹ̀ ọ̀rọ̀ fún ẹka-ìmọ̀ náà..
wikipedia
yo