cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àwọn tí wọ́n ń fi èdè Gẹ̀ẹ́sì kọ̀wé máa ń lo èdè ìperí "logy" lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan (ìlò “Tratyllogy” kò sì fi bẹ́ẹ̀ wọ̀ pọ̀) láti pe ìmọ̀ aáyan-ògbufọ̀, èdè ìperí tí o sì bá èyí mu nínú èdè Faransé ni "Trabugbẹ́kẹ̀lọ] (gẹ̀gẹ̀ bi Société française de Traduyágágálo ségie ṣe sọ)..
wikipedia
yo
Ni United States, o tẹ́ wọn lọ́rùn lati lo ede ìperí "Imo A-ògbufọ̀ àti Tapita" (Gẹgẹ bi o se wa ninu American Translation and Interpreting Studies Association), bi o tilẹ jẹ pe isedale imo yii ni Europe naa maa n soro Tapita gege bi akoonu imo Ore-ògbufọ̀ (Gẹgẹ bi o se wa ninu European Society for Translation Studies Ajo Imọ Ore-ògbufọ̀ ti Ile Europe).Awọn iwadii ibẹrẹ Gẹgẹ bi itan se so, imo aa-ògbufọ̀ ti Wa, o pe gehge bi “Oluye” (ti o n sọ bi awọn ògbufọ̀ ṣe le ṣe igburun), titi ti o fi de ọ̀gangan pe awọn àsáró ti o jẹmọ aáyan-ògbufọ̀ ti ko fi ti iwoye (ifiṣe) ko di itẹwọgba gege bi àsáró nipa aa-ògbufọ̀ rara..
wikipedia
yo
Nigba ti awon onpìtàn nipa imo AÁYAN-ògbufọ̀ tọpasẹ̀ ero ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ awon ero ile apa iwo-oorun nipa AÁYAN-ògbufọ̀, Bí àpẹẹrẹ, wón máa ń lo ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ rẹ̀ mọ́ ọ̀rọ̀ gbajúmọ̀ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ ní Cicero nípa bí ó ṣe ṣàmúlò aáyan-ògbufọ̀ láti inú èdè Greek sí Latin láti jẹ́ kí ipa ìṣòwòsoro rẹ̀ le gbèrú si — èyí tí ó jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ ohun ti Jérôme padà pè ní AÁYAN-ògbufọ̀ ìfòye-di-oye..
wikipedia
yo
Ìtàn ìṣàpéjúwe àwọn tàpita ni Egypt tí Herodotus sọ ní òpó Tẹ́lẹ̀ sẹ́yìn kì í ṣe èyí tí wọ́n gbà lérò ní ìlànà ìmọ̀ fọ́-ògbufọ̀ — ní apá kan torí kò fi ìlànà aáyan-ògbufọ̀ ṣiṣẹ́ sílẹ̀ fún àwọn ògbufọ̀ láti mọ ìlànà ṣíṣe ígbugbu..
wikipedia
yo
Ní China, ìtàkùrọsọ lórí bí wọ́n ṣe ìgòǹ bẹ̀rẹ̀ láti ìlànà títú Buddhist Sutras ní àsìkò tí ìran hàn ń ṣèjọba.Àwọn ìpè fún iṣẹ́ àti akitiyan ìmọ̀ akadá ní 1958, ní ibi Àpérò àwọn SEÉfì Kẹrin ní Moscow, àríyànjiyàn nípa ìlànà lìngúísíìkì àti lítíréṣọ̀ tìwà ṣe aáyan-ògbufọ̀ dé ọ̀gangan ibi tí wọ́n ti dábàá pé ohun tí ó dára jùlọ lè jẹ́ láti ní ìmọ̀ sáyẹ́ńsì tí ó nípa láti ṣàlàyé gbogbo onírunrú ìmọ̀ nípa aáyan-ògbufọ̀, láìṣe pé ó fi gbogbo ara mọ́ ìmọ̀ lìngúísíìkì tàbí kí ó fi gbogbo ara mọ́ ìmọ̀ lítíréṣọ̀..
wikipedia
yo
Lagbo ìmọ̀ Isafiwéra Lítíréṣọ̀, àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Aké-ògbufọ̀ ni wọ́n gbé lárugẹ láàrín ọdún 1960 ní àwọn Fásitì ilẹ̀ Amẹ́ríkà kọ̀ọ̀kan bí Fásitì ti Iowa University of Iowa àti Princeton.Láàrín ọdún 1950 sí 1960, fífi ìmọ̀ lìngúísíìkì Ajémeto kò ìmọ̀ àtì-Ógù bẹ̀rẹ̀ sí ní gbòde..
wikipedia
yo
Ní 1958, Onímọ̀ lìngúísíìkì ọmọ ilẹ̀ Faransé Jean-Paul Oyèy àti Jean DarbelNet ṣe àfiwéra èdè Faransé àti Gẹ̀ẹ́sì ní 1964, Eugene nidà ṣe àtẹ̀jáde toward a Science of translating, tí ó jẹ́ atọ́nà fún ìlànà aáyan- ògbufọ̀ Bíbélì èyí tí ó kó ìmọ̀ púpọ̀ lára iṣẹ́ Harris transforonal Grammar..
wikipedia
yo
Catford ṣe ìmọ̀ aáyan-ògbufọ̀ oníTíọ́rì nípa ìwòye Irinrẹ̀tí.ní gbèdéke rànibùsùn àti ní ìbẹ̀rẹ̀1970, onímọ̀ orílẹ̀-ẹ́ Czech tí ó ń jẹ́ Orílẹ̀ja Levy àti àwọn tí ilẹ̀ Anton pópónípakúpa àti frántíSek MIKO ṣiṣẹ́ lórí ìmọ̀ Lolo-èdè AÁYAN-ògbufọ̀ ajẹmọ́lítíréṣọ̀.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
National Hospital Abuja jẹ okan lara awon ile iwosan ni Abuja, FCT, Nàìjíríà.A da ile iwosan naa kale labẹ eto family support Programme Initiative..
wikipedia
yo
Abdullámì AbukaBaka ni eni ti o se ǹobi ile iwosan naa ni 22 May 1999..
wikipedia
yo
Orúkọ tí wọ́n kọ́kọ́ fún ilé ìwòsàn náà ní National Hospital for Women and Children..
wikipedia
yo
Ijoba fun ile iwosan naa ni orukọ ti o un je lowo ni ojo kewa osu karun-un(10 May) odun 2000..Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Kylian Mbappé Lottin (ti a bi 20 Oṣu kejila ọdun 1998) jẹ agbabọọlu fun Faranse kan ti o n gba iwaju fun egbe Ligue 1 Paris Saint-Germain ati ẹgbẹ orilẹ-ede France..
wikipedia
yo
A ka si ọ̀kan ninu àwọn agbabọọlu ti o dara julọ ni agbaye, o jẹ olokiki fun àwọn ege ti o ma n ge, ati iyara gbe bọọlu rin rẹ..
wikipedia
yo
A bi ni Ilu Paris, o dagba ni Bondy, Mbappé bẹrẹ si n gba boolu fun Monaco ni odun 2015, nibiti o ti gba akole Ligue 1..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2017(o jẹ ọmọ ọdun mejidinlogun nigba naa), Mbappé fowo si iwe pelu egbe agbaboolu Paris Saint-Germain leyin adehun lati ra fun € 180million, eyi mu ki o je agbaboolu keji ti o gbowolori julọ ati ọdọ agbabooluti ti o gbowolori julọ.Àwọn itọkasiàwọn apapọ alààyẹ̀ awon Ọjọ́ìbí ni 1998..
wikipedia
yo
RAM Titanic jẹ́ ọkọ̀ ojú omi ń kan tí ó rí sí òkun North Atlantic ní ọjọ́ kẹdọta Oṣù ké(15 April) ọdún 1912 lẹ́yìn igba tí ó kọ òkúta omi didi kan nígbà tí ó rin irin ajo láti southampton, England sí New York City, orílẹ̀ èdè America..
wikipedia
yo
Lára àwọn arin irin àjò 2,224 ti ó wà ninu oko naa, ó lè ni 1,500 sọ ẹ̀mí wọn nu...
wikipedia
yo
OnyeBüchi Olanieh, tí àwọn ènìyàn Mo mọ́ orúkọ orí-ìtàgé rẹ̀ Büchi (won bi í ní April 4, 1979) jẹ́ apanilẹ́rìn-ín Nàìjíríà, A-kọ-orin-sílẹ̀, onkọ̀wé, àti òṣèré láti Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà , Nàìjíríà . Ìgbén-ayé àti Èkó á bí Ochi ní Kwale Komọ̀ West West, Ìpínlẹ̀ Delta, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O lo D.S.C Nursery and Primary School ati Ovwian Secondary School ni Ovwian, Warri..
wikipedia
yo
Leyin eko iwe mewaa re, o lo Bendel State University (ti a mo si Ambrose Alli University ni bayii), nibi ti o ti kẹkọọ nipa imo ofin (Law).Iṣẹ apanilerin-in Büchi bere ise apanilerin-in re ni 2008, leyin ti won mu u mo apanilerin-in tẹ̀ẹ́-a, ti o pe itage si ibi ere rẹ tẹ̀ẹ́-a live n Naked..
wikipedia
yo
Eyi lo ṣaaju ipade pẹlu awọn apanilerin-in miiran bi i Ali Baba ati Ọ̀pá Williams, ti o fun Büchi ni aye ni Nite of a 1000 Laughs Show re..
wikipedia
yo
Büchi ti sise pelu awon apanilerin apanilerin-in miiran bi i i go dye, I Go Save, Basket ati Bovi, lara awon miiran .Awon ami-eye Standúp Comedian of the Year Award Award of the Yéarawọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Michael Sani Amanesi, tí inagígé rẹ̀ jẹ́ Mc lively jẹ́ òṣèré àti ọ̀sẹ̀fẹ́ kan ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfàdínlógún oṣù kẹjọ, ọdún 1992, tí ó jẹ́ ọmọ Agenebodè ní ìpínlẹ̀ Ẹdó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbé ayé àti ètò ẹ̀kọ́ Ẹ̀wọ̀ọn bí Mc lively sí ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ibi tí ó ti ka ìwé alakọbẹrẹ ní ilé ìwé alakọbẹrẹ tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Isùn àti ilé ìwé sẹ́kọ́ndírì tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Mọ́remí..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn kíka ìwé sẹ́kọ́ndírì, ó tẹ̀síwájú láti lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Fásitì ti Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ní ilé Ifẹ̀, níbi tí ó ti kàwé gboyè nínú iṣẹ́ òfin (Law), lẹ́yìn tí wọ́n pè sí Nigerian Bar ní ọdún 2016,èyí tí ó kọ sílẹ̀ láti ṣe iṣẹ́ ẹ̀fẹ̀.Iṣẹ́ Komedi àti fíìmùo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Komedi ní ọdún 2015, tí ó sì jẹ́ mímọ́ láti ara ẹ̀fẹ̀ kan tí ó ṣe, tí ó pè ní "agidi" níbi tí ó ti ṣe nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.MC lively ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn gbajúmọ̀ tí wọ́n ń ṣe iṣẹ́ ẹ̀fẹ̀ bí tirẹ̀, àwọn bí Akporọrọ, GoSave, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
O jẹ́ ọ̀kan lára akópa nínú fíìmú tí àkọlé rẹ ń jẹ́ "Seven and half date” ní ọdún 2028, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ James, Ẹnìkejì tí o fẹ́ fẹ́ Bsola.
wikipedia
yo
Òun náà sìni Dele nínu eré àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Fate of Alákadá"
wikipedia
yo
And featured in the 2022 Film survivors.Àwọn àmì ẹ̀yẹRoyal African Youth Leadership Award given by the Ọọ̀ni of Ifẹ̀Adéyẹyè Ẹnitàn Ògúnwúsìcity People Music Award for Comedy Act of the Yéarawọn mìíràn àtòjọ àwọn aláwàdà ọmọ NàìjíríàÌwé Ìtọ́kasí Birth Birth Ènìyàn Alààyè, Málé Cocean Awólọ́wọ̀ University Aludọ́gba Actors From Osun Stata-tẹni film Actors-21st Nigerian Law -21st Nigerian Malé Actors Internet celebrities..
wikipedia
yo
Bright Okpocha (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹsan-an ọdún 1978 ní ìpínlẹ̀ Èkó), tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Basketmouth tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí, jẹ́ Rèbékàriin àti òṣèré ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O ti ṣeto awọn ere orin awada Ìmúrasílẹ̀ Olókìkí bíi "Basket unCenunted" káàkiri àgbáyé.Basket ti gbàlejò ní onfẹ̀ awada kan lori Instagram gram, tí a pè ní "Things èyí tí ó fa ariwo láti ọ̀dọ̀ àwọn olólùfẹ́, lẹ́hìn tíá ìgbà kan tí fi tí fidio kan hàn tí ó sọ àwọn nǹkan àìràbalẹ tí ó jọmọ ìbálòpọ̀, pẹ̀lú ọmọ kan ní wiwo isunmọ nínú fidio náà.Ó jẹ́ olùolùpilẹ̀ṣẹ̀ ti “Ghana tẹ́lẹ̀ tí “Ìtàn ayé rẹ̀ ayé rẹ̀ Ìpínlẹ̀ rẹ̀ ní wọ́n bí Supari Okcha ṣùgbọ́n ó wá láti Ìpínlẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó parí ilé-ìwé alakọbẹrẹ àti Ilé-ẹ̀kọ́ ti girama ni Apapa, Ìpínlẹ̀ Èkó, ó sì lọ sí Fásitì ti Benin, Ìpínlẹ̀ Edo láti kọ́ ẹ̀kọ́ fún ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ nípa “sociology” àti “ANIDX|
wikipedia
yo
O se awari ogbon rẹ ni Ilu lilu ni ọdun 1991 pẹlu atẹle nipa gbigbe “Ukun” ni ọdun 1994..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn náà ó dá ẹgbẹ́ kan tí a pè ní "dá Syhophatts tí ó ní àwọn ọmọ ẹgbẹ́ méje àti pé wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí lọ fún eré àti “O-Ukòb" ní ọdún 1995, sibẹsibẹ wọ́n yapa ṣaájú ìdásílẹ̀ èyí ohun elo k'ọ́kan..
wikipedia
yo
Basketmouth farahan ninu iṣafihan Africa Magic "My FlatMates ni ọdun (2016).láìpẹ́ yii Basketmouth ti gbalejo olówó ati ọlọ́lá Naijiria Femi Otedola ni ile rẹ..
wikipedia
yo
Ní oṣù kejìlá ọdún 2020, ó bẹ̀rẹ̀ jara eré àwàdà rẹ̀ tí àkọlé “Pápá Benji” Tirení Oṣù Kọkànlá Ọdún 2010, Basket fẹ́ ọrẹ-bìnrin rẹ̀ tipẹ́ Elsie ní ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n ní ọmọ mẹ́ta papọ̀.Ní oṣù Kejìlá ọdún 2022, Basketmouth kéde nípasẹ̀ àkọọ́lẹ̀ Instagram iṣẹ́ rẹ̀ pé òun àti ìyàwó rẹ̀ n kọ ara wọn sílẹ̀ lẹ́hìn ọdún méjìlá ti ígbéyàwó.Àwọn ààmì ẹ̀yẹ àti yíyanàwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Henry Oloyede Fajemirokun, CON jẹ ògbóǹtarìgì oniṣowo orilẹ-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Wọ́n bí i ní ọjọ́ kẹrindinlọgbọn, oṣù keje, ọdún 1926..
wikipedia
yo
Òun pẹ̀lú Adebayo Adédèjì ní ìgbàgbọ́ nínú ètò-ọ̀rọ̀-ajé láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí Ìwọ̀-Oòrùn Áfíríkà èyí tí ó di ohun tí à ń pè ní Economic Community of West African States (kúkúrúWas).Ó rí ìdí fún ilé-iṣẹ́ aládàáni láti wá, ó sì pèsè àwọn ilé-iṣẹ́ aládàáni..
wikipedia
yo
O mu ki awon irise ti eto-oro-aje nilo ni orile-ede Naijiria, iwo-oorun Afirika, ati Commonwealth gbérù si i.O je olori waju ti Nigerian Association of Chambers of Commerce, Industry, Mines and Agriculture (NAccima), olori ẹlẹ́ẹ̀kẹfà ti Lagos Chamber of Commerce and Industry, Olori akoko ti Federation of West African Chambers of Commerce (1972-1978) ati olori oludasile Nigerian-British Chamber of Commerce (NBCc) pelu sir Adam Thomson, Alaga British caledonian Airways eyi ti o wa lara British Airways)..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìgbìmọ̀ àwọn gómìnà àti olórí tẹ́lẹ̀ rí ní Nigerian-American Chamber of Commerce (NACC)..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ olórí fún, Federation of Commonwealth Chambers of Commerce.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀..
wikipedia
yo
Mama rẹ̀ jẹ́ ọmọ olóyè ńlá tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ Ọ̀dọ̀fin Obubule Akinabén.Ile-iwe St.Peter's, ní ilé-ì àti ilé-ìwé tí orúkọ rẹ̀ tẹ́lẹ̀ tẹ́lẹ̀ jẹ́ St's, òkè-ò ní ó ti ka ìwé mẹ́fà rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó ka ìwé mẹ́wàá rẹ̀ ní CMS Grammar School, Lagos àti ni Òndó Boys High School (1942-1944)..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tó parí ìwé rẹ̀ ní Òndó Boys School, ó darapọ̀ mọ́ Royal West African Fronative Force ní ọmọ ọdún mejidilogun..
wikipedia
yo
O si si ilu ni ile India ni asiko Ogun Àgbáyé keji..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ogun náà ni ó darapọ̀ mọ́ ẹ̀ka Post and Telegraph Department gẹ́gẹ́ bí i òṣìṣẹ́ , ó sì kàwé ní ìkọ̀kọ̀ fún ìwé-ẹ̀rí ilé-ẹ̀kọ́ Cambridge.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Quinton Aaron (tí a bí ní ọjọ́ karùn-úndínlógún Oṣù Kẹjọ, Ọdún 1984) jẹ́ òṣèré orílẹ̀-èdè American Actor..
wikipedia
yo
Ó ṣe fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ nínu eré Michel Ggon tó ń jẹ́ bẹ́ kind rẹ̀windwind..
wikipedia
yo
ẹ̀dà-itan tó kọ́kọ́ ṣe ní ibi tí ó ti ṣe Michael Oher nínu fíìmù kan ní ọdún 2009 tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́The Blind Side.ibẹrẹ Aye rẹ̀ a bí Aaron sí The Bronx, New York City, amo ó kó lọ sí Augusta, Georgia lẹ́yìn tó parí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀.Àtòjọ fíìmù àgbéléwò rẹ̀:Orí Amóhùn-máwòrán Àwọn Olorin Olorin Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Wole Oládiyun ti ojo ibi je ojo keji osu kerin odun 1959, je alufaa kan ni orile ede Naijiria, onkowe, onisowo, imo ero (Ṣebíeer) ati oludari/oludasile ile ijosin ti oruko re n je Christ of Living Spring Apostolic Ministry (Claaye). Igbe Aye ati eto ekoalufaa Oládiyún je omo bibi ile oluji ni ipinle Ondo ni orile ede Naijiria ti oju ibi re si je ojo keji osu kerin, odun 1959..
wikipedia
yo
Àwọn òbí rẹ̀ méjèèjì jó àlùfáà ilé ìjọ́sìn, nígbà tí baba rẹ̀ jẹ́ alàgbà, tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ Dikìnesí ní ilé ìjọ́sìn Àpósítélì ti Kírísítì (Christ Apostolic Church)..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ìmọ̀ ẹ̀rọ ní Fásitì tí ó wà ní ilẹ̀ Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú láti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè mbá ní Netherlands Business School ní Holland.Iṣẹ́ ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Fásitì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ní ilé Ifẹ̀, àlùfáà Oládiyún bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ títa paàti ọkọ̀, àwọn kẹ́míkà àti igi èyí tí kò wà ní ìbámu tàbí lọ́nà oun tí ó pinnu láti ṣe tí ó wà lọ́kàn rẹ̀ tii ṣe iṣẹ́ ọlọ́pàá.Iṣẹ́ ìránṣẹ́ àlùfáà Oládiyún lósì Latter rain Bible School tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Bákan náà, ó fi ara rẹ̀ sílẹ̀ láti di ìgbà kejì Rev..
wikipedia
yo
D.K Aboderin tii se alufaa agba ní Faith Family Bible Church, tí ó wà ní Obùba ní ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Ó mú àlùfáà Matthew aṣimolówó gẹ́gẹ́ bí olùtọ̀nà nínú iṣẹ́ ìránṣẹ́.Ìgbé ayéàlùfáà Oládiyún ṣe ìgbéyàwó ní ọdún 1990 pẹ̀lú Bùkọ́lá Oláyunyún tí òun náà jẹ́ àlùfáà nínú iṣẹ́ ìránṣẹ́ àlùfáà Oládiyun..
wikipedia
yo
Wn si jọ bi ọmọ mẹrin papọ ti wọn si ni awọn ọmọ-ọmọ mẹta.Awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Ira Frederick Aled-fú (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje, ọdún 1807, tí ó sì di olóògbé ní ọjọ́ keje oṣù kẹjọ, ọdún1867) jẹ́ òṣèrékùnrin àti adarí eré orí-ìtàgé tó wá láti orílẹ̀-èdè American..
wikipedia
yo
Ó di ìlú-mọ̀ọ́-ká látàrí fífi ẹ̀dà-ìtàn Shaalátakòate hàn..
wikipedia
yo
James HewLett ati Aledtorí ni a le pe ní àwọn Aláwọ̀-dúdú akọkọ ti wọn maa n se ere apanilẹ́kún.ibẹrẹṣe aye ati iṣe rẹ Ilu New York City ni won bi Aled- si, sinu idile iranṣẹ Ọlọrun Daniel ati Luranah, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu keje, ọdun 1807..
wikipedia
yo
Àmọ́ àwọn ìwé kan sọ pe wọ́n bí sí Bel Air, Maryland.Iṣẹ́ Aled- akọkọ waye ni ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ọdun 1820 pẹ̀lú Ile-iṣẹ Afirika kan, èyí tí William Henry Brown àti James HewLett ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ni osu karun-un, odun 1825, nigba ti o pe Ọmọdun mẹ́tàdínlógún, Aled- se ifarahan akoko re si ilu London lasiko ti won fe se agbejade fiimuocasal..
wikipedia
yo
ní oṣù kẹwàá ọdún 1825 Bákan náà, Aled- tún ṣiṣẹ́ gọbọi mìíràn ní London Royal Coburg Theatre, ó sì di Aláwọ̀-dúdú Akoko ti a ṣe idasilẹ ara rẹ ni ilẹ̀ ajeji..
wikipedia
yo
Ó ṣe ọ̀rọ̀ọ́n nínú fíìmù The rẹ̀vovolt of Surinam, or a slave's revenge.Ìdílé Aled- ira Daniel Aled-kán, 1847-?
wikipedia
yo
Amanda Christina Elizabeth Aledtorí (Amanda ira Aled€$)), 1866-1956..
wikipedia
yo
Olórin opera, ònkọ̀wé àti a-ṣẹ̀dá-orin lábẹ́ Montague Ring.
wikipedia
yo
Rachael Margaret Frederika Aledṣíṣàṣàrò, B.interpret; o ku ni igba ewe rẹ ni ọdun 1869.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Mark Alexander knox (tí a bí ní ọjọ́ karùndínlógún Oṣù Kẹrin, Ọdún 1970), tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí Flex Alexander tàbí Flex, jẹ́ òṣèrékùnrin, Logu-in, àti oníjó láti orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó béèrè iṣẹ́ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán ní ọdún 2001 sí ọdún 2006..
wikipedia
yo
Wọ́n jọ bí ọmọ méjì, obìnrin kan, Ìmánì Shekinah Alexander-Knox (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹjọ, ọdún 2001) àti ọmọkùnrin Elijah Alexander-Knox (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kẹta, ọdún 2004)..
wikipedia
yo
Alexander jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Phi beta síma.Àtòjọ àwọn fíìmù àgbéléwò rẹ̀:Orí àmólẹ̀-máwòrán àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Harriet René "Khandi" Alexander (ti won bi ni ojo kerin osu Kesan-an, odun 1957) je onijo, akonimọojo ati osere orile-ede American..
wikipedia
yo
O beere ise re gege bii onijo ni odun 1980s, o si beere ise akonimoojo fun Whitney Houston lati odun 1988 wo 1992.Àtòjọ awon fiimu refiimuori ero-amóhùn-máwòrán olorin olorin 1993 - "Heaven knows" by Luther VAndssato awon ami-eye rẹàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mark Angel (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n Oṣù Karùn-ún, Ọdún 1991) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn gbajúmọ̀ aláwàdà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ mọ fun awọn ere awada Mark Angel Comedy series ni ori ikanni YouTube, eyi ti oun ati awọn ara ile rẹ bi Emmanuella Samuel, ati "Aunty" Success Mawibuike..
wikipedia
yo
Ìkànnì Mark Angel ní ikanni awada àkọ́kọ́ ni Afrika lati ni olólùfẹ́ milionu kan.ipilẹ rẹ a bi Angel ni Port Harcourt, Rivers State, Nigeria ni ọdun 1991..
wikipedia
yo
Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ gbà a wọlé fún ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìṣègùn Òyìnbó ṣùgbọ́n àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó fẹ́ ràn án lọ́wọ́ papòdà ní ọdún kan náà, èyí mú kí ó má le tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
O pada lọ si orile-ede India lati ko nipa yíyàwòrán fiimu ki o to pada si Naijiria lati ni imo si nipa ise naa sugbon ko ri ise ti o n san owo ti o te lorun ni Nollywood..
wikipedia
yo
Maryam àpàọkàgi, ti àwọn ènìyàn mo si taaooma, jẹ́ apanilẹ́rìn-ín orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó tún jẹ́ ayàwòrán lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, òun ni olùdarí àti olùdásílẹ̀ Chop Tao, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ oúnjẹ, ó sì ń darí ilé-iṣẹ́ Greenade Ó di gbajúgbajà látàrí àwo eré Ibiv-in rẹ̀ lórí ẹ̀rọ Ayárabíàṣáìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀. ayé rẹ̀..
wikipedia
yo
A bí Maryam Apaọkàgi ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù Kejì, Ọdún 1999 sí ìlú rẹ̀ ní Ìlọrin, Ìpínlẹ̀ Kwara, amo ó lo ìgbà èwe rẹ̀ ní Nàkò́n..
wikipedia
yo
O kẹkọọ nipa Tourism and Travel Service Management ní Kwara State University..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2022, o sọ fun iwe-iroyin The Punch pe, "Mo fẹ́ di Dókítà, mo si tun yi i pada si agbẹjọro..
wikipedia
yo
Àmọ́ ẹ̀kọ́ Tourism ni wọ́n fún mi láti lọ kọ́ ní ilé-ìwé”.Ìgbésí ayé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ni osu kẹwàá, odun 2020, won fi apaọkàgi fun oko àfẹ́sọ́nà re, ti i Seturola;” OlaDimeji (ti a tun mọ si..
wikipedia
yo
Abula) ní Nà́àsí, wọ́n sì ṣe ìgbeyàwó ní Ọjọ́ Èlélógún Oṣù Kìíní, Ọdún 2021. Ọdún-Àwo rẹ̀-tún wo Wo Àto Ànilè àwọn Ọmọ ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Kolópọ̀ Kehinde Peter, tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Kenny Blaq, jẹ́ olorin àti apanilẹ́rìn-in orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
ó ṣeré níbi ayẹyẹ kejì ti Naija independence àti ayẹyẹ àṣekágbá ti Africa Magic.ibẹrẹṣe ayé rẹ̀ Kenny Blaq kàwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ni Ejigbo, ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Ó ní láti kúrò ní SS3 láti lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ mìíràn nígbà tí àwọn òbí rẹ̀ ò lè san owó ilé-ìwé rẹ̀ mọ́.Ó kẹ́kọ̀ọ́, ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí agbéròyìn sáfẹ́fẹ́ ní ilé-ìwé FRCN ní Ìpínlẹ̀ Èkó.Iṣẹ́ rẹ̀ Blaq bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ apanilẹ́rìn-in rẹ̀ ní ọdún 2008, ó sì ti ṣeré lọ́pọ̀lọpọ̀ ayẹyẹ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti lókè òkun bí i i Laff pẹ̀lú Mc bínú, Gbenga Adeyinka (Laffmatèdè), Ali Baba's & Finá – Ali , MC Amana's (dispemúlẹ̀mófo Me), Cool FM praise Jam, Darey's Love Like a Movie, Ay Live, Basket's (Lord of the ribs), Africa Laughs (Uganda), ṣèkà live (Rwanda) Rív35 (Sierra Leone) àti Benin GGLO Laffta Fest (Nigeria)Ayẹyẹ apanilẹ́rìn-in tó jẹ́ tirẹ̀ gan-an tó pè ní The BóyáMórọ̀n of KennyBlaq gba ami-ẹ̀yẹ eré apanilẹ́rìn-in tó dára jù lọ ní ọdún 2017 àti 2018.Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ajiọnà Alexus Brown (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógun Oṣù Kẹta, Ọdún 1996) jẹ́ òṣèrébìrin orílẹ̀ èdè America tó di ìlúmọ̀ọ́ká látàrí ifarahan rẹ̀ nínú eré The Rickey Sleyley, Empire, 13 Reasons Why, Aroko, and Breaking ín..
wikipedia
yo
O bẹrẹ iṣẹ yii ni ọdun 2008, nigba to pe Ọmọdun mejila.ibẹrẹṣe aye rẹ wọn bi Alexus ni ọjọ kerindinlogun Oṣu Kẹta, ọdun 1996, si tuske, ni Alabama..
wikipedia
yo
O kẹkọọ gboye ni Alabama School of Fine Arts, nibi ti o ti kẹkọọ nipa ere ori-itage.iṣẹ rẹ ni ọdun 2021, o farahan ninu ere Starz, pẹlu Russell Eduby, Da'vin, Demetrius Flenoary Jr., Eric Kofi-Abréfà, ati Michole fòpinsi White.Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀ Retọ́ka ẹ̀rọ-Amóhùn-máwòrán orin Jadramúramùsórin ÀdàkọproYẹ Singlesáwọn Fọ́nrán Orinawọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Sam Loco Efe (ti a bi ni ojo karundinlogbon osu kejila, odun 1945, to si di oloogbe ni ojo keje osu keje, odun 2011), ti oruko àbísọ re n je Sam Loco Efèén ke ti won bi ni Ipinle Enugu je òṣèrékùnrin ati oludari ere.ibẹrẹ aye ati eto ẹkọ rẹ won bi Efe si Ipinle Enugu, o je omo arase Efewonkíyèke..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Benin, tó ń ṣiṣẹ́ ní apá ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ oníṣòwò, tó ń ta àkàrà..
wikipedia
yo
ó pàdánù bàbá rẹ̀ nígbà tó wà ní ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, èyí sì mú kí ó lo ọ̀pọ̀ ọdún ju bí ó ti yẹ lọ láti kàwé rẹ̀ tán nítorí ó ní láti ran ìyá rẹ̀ lọ́wọ́ níbi òwò rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìrírí àkọ́kọ́ rẹ̀ sí eré orí-ìtàgé bẹ̀rẹ̀ nígbà tí àwọn ẹgbẹ́ onítíátà kan wá sí ilé-ìwé wọn láti wá ṣe eré orí-ìtàgé kan tí wọ́n pe àkọ́lé rẹ̀ ní The Doctor in spite of himself..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn eré náà, ẹefe pinnu láti darapọ̀ mọ́ ẹ̀gbẹ́ náà..
wikipedia
yo
Látara èyí, ó bá wọn ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré orí-ìtàgé, ó sì gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ.Àtòjọ àwọn fíìmù àgbéléwò rẹ̀ Tom and Jerry (With Chinedu Ikedieze and Osita Iheme) Owo Blow I'll Take My Chances Final World Cup Long John Ukwa OOṣùfia in London My Love I Want To Harvest You the Return of anunuse Things Fall Apart Nneka the Preru Serside Old School A Fool at 40 Blood Billionaires 2 mẹ́rin must Obey my Loveàwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Dakópawunon "Noni" Tristan Madueke (won bi i yojo ke osu keta odun 2002) je agbaboolu-sise omo orile-ede England ti o n gba boolu fun iko egbe agbaboolu-sise £v Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Duncan Wene Mighty Okechukwu (won bíi ní Ọjó kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹwàá ọdún 1983), eni tí a mọ̀ sí Duncan Mighty, jẹ́ olórin orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, akọrin àti onibo orin lati ìlú Obio-Akpor, ní ìpínlẹ̀ Rivers..
wikipedia
yo