cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Yàtọ̀ sí Moi-Moi tí wọ́n ń pèé ní ilẹ̀ Yorùbá, wọ́n tún ń pèé ní Alelé, tàbí ọ̀lẹ̀lẹ̀’’ ní apá orílẹ̀-èdè Sierra Leone àti Ghana ..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ma ń jẹ mọ́ìmọ̀i pẹ̀lú ẹ̀kọ́, kókó lọ́dọ̀ àwọn Hausa tàbí ògì..
wikipedia
yo
Tukọjá (also spelled tubani) is a similar dish found in northern Ghana..
wikipedia
yo
Wọ́n lè fi mọìmọ̀i mu gàrí pẹ̀lú, wọ́n sì tún ma ń fi gbádùn oúnjẹ bíi ìrẹsì joloofu, ìrẹsì ọ̀fadà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn èròjà mọìmọ̀ìwọ̀n lè lo ẹ̀wà pupa, ẹ̀wà ṣẹ̀ṣẹ̀, tàbí ẹ̀wà funfun tí wọ́n ń pè ní erèé, wọ́n ma ń fi ata, epo, òróró, edé, àlùbọ́sà, ẹyin, ẹja yíyan, iyọ̀, Magi tàbí ẹran tí wọ́n ti bọ́ sí kí ó lè ládùn tó dára.Bí a ṣe ń pèsè mọìmọ̀i wọn ma ń pèsè mọìmọ̀i pẹ̀lú kí wọ́n kọ́kọ́ rẹ ẹ̀wà èyíkéyí tí wọ́n fẹ́ lọ̀ sínú omi tútù títí yóò fi rọ, lẹ́yìn náà wọn yóò bọ́ epo ara ẹ̀wà náà kúrò.Lẹ́yìn èyí ni wọn yóò lòó kùnà, wọn yóò wá fi àwọn èròjà tí a ti mẹ́nu bà ṣáájú..
wikipedia
yo
Àwọn míràn ma ń fi ẹ̀yin, ẹran bíbọ̀, èdè àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ kún kí ó le dùn yùngbà yungba..
wikipedia
yo
irúfẹ́ mọ́ìmọ̀i tí wọ́n bá pèsè pẹ̀lú àwọn èròjà tí a ti ká sílẹ̀ yĩ ni a lè pè ní moìmọ̀i ẹlẹmi méje..
wikipedia
yo
Wọ́n má ń ṣu mọ́ìmọ̀i rógódó, tabi kí wọ́n ṣú u pẹrẹsẹ, ó dá lórí ohun tí wọ́n bá fi sú u..
wikipedia
yo
bí wọ́n bá ti fi sínú ohun tí wọ́n fẹ́ fi sú u tan, wọ́n yóò sì gbé sí orí iná..
wikipedia
yo
Tí wọ́n bá fi ewé ẹran tàbí ewé ẹ̀bá tàbí ewé ọ̀gẹ̀dẹ̀ ṣú mọ́ìmọ̀i ni yóò jẹ́ kí ó rí rógódó..
wikipedia
yo
Joy Bryant, gẹ́gẹ́ bi í orúkọ rẹ̀, jẹ́ òṣèrébìnrin, oníṣòwò, àti ìsẹ́-oge ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó ti kópa tàbí farahàn nínú-un ogunlọ́gọ̀ eré àti iṣẹ́ẹ mohun-máwòrán láti ìgbà tó ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ẹ rẹ̀ ní ọdún 2001..
wikipedia
yo
A bí í ní Ọjọ́kejidinlogun Oṣù Kẹwàá Ọdún-un 1974 sí Bronx, Ìpínlẹ̀ New York..
wikipedia
yo
Arúgbóbìnrin òbí i rẹ̀ ló tóó dàgbà; ìyá yìí náà ló sì pèsè ohun gbogbo fún-un kí ó tó wá dẹni tó rọ́wọ́Hori..
wikipedia
yo
Ọmọ ọdún mẹ́ta ló sì ti máa ń dáwọ́ ìjọ gẹngẹ ni fífi ẹ̀bùn àtinúdáa rẹ̀ hàn..
wikipedia
yo
Ní kiká, ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ gẹ́gẹ́ bi i idanimọ lọwọ ajọ NAACP fun Image Award nominations; Ewe, ó tún ti gba ọkan fún screen Actors Guild Award Nomination.iṣẹ rẹ..
wikipedia
yo
Dewon bere ise re gege bii onise-Oge lara pe o farahan ninu awon ipolowo fun "Ralph Lauren", "Tommy Hilfiger", "gap Inc." ati "VictoriaVictoria's Secret"
wikipedia
yo
Lẹ́nu iṣẹ́ẹ fiimu, ó ní alájà nígbà tí ó kópa nínú-un eré kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Antwọ́nẹ Fisher" ní ọdún 2002, èyí tí ó tówóọ̀ denzel Washington jáde..
wikipedia
yo
Awon ere miiran to tun ti kopa ni "4òrùn-man 2" ni odun-un 2004, "The Skẹ̀lẹ̀ton key", "GE rich or die Corls" ati bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn itọkasi...
wikipedia
yo
Keith Richards [kith ‘riəə] 1, tí a bí ní oṣù kejila ọjọ 18, ọdún 1943 ní Dartford, Kent (England), jẹ́ akọrin ará ìlú Gẹ̀ẹ́sì, akọrin, onigita, olùdásílẹ̀, ní ọdún 1962, pẹ̀lú Ojúgun Jasínté, Brian Jones àti Ian Stewart, tí ẹgbẹ́ Apata the sẹ̀sẹ̀ òkúta..
wikipedia
yo
Papapo pẹlu kiniun jasín, ni ajọṣepọ kan ti wọn pe ni awọn Twins GLim, o ko pọ julọ ti ẹda atilẹba ti ẹgbẹ naa..
wikipedia
yo
O tun jẹ oṣere kan, ti o ṣe pataki baba Jack Sparrow (ti o se nipasẹ Johnny Dpp ti o ni atilẹyin pupọ nipasẹ rẹ lati ibẹrẹ fun aṣọ rẹ) ni awon fiimu meji ni awon ajalèlókun ti Kariìdáláre jara.Keith Richards ti kọ olokiki rẹ lori ṣiṣere Gìtá Kimo rẹ (lilo Ṣíṣàtúnṣe Sisi ni G, nipa yíyọ Okun 6th ti ohun elo kuro pẹlu òrùka ti ), eyiti o jẹ ki o jẹ olupilẹṣẹ aroso ti awon riffs, lori nọmba nla ti awọn débá kariaye ti o kọ pẹlu Karun Jalad ( 14 ti awọn orin du wa laarin awọn orin 500 ti o tobi julọ ni gbogbo igba nipasẹ iwe irohin Rolling Stone, eyiti o tun ṣe ipo rẹ 4th ti o dara julọ onigita ti gbogbo akoko akọkọ), ati lori iṣẹlẹ aye rẹ, ọpọlọpọ awọn iṣoro rẹ pẹlu eto idajọ ni awọn orilẹ-ede pupọ-ede nitori si àfẹ́di rẹ si heroin ni awọn ọdun 1970..
wikipedia
yo
>LẹhinLẹhin ọgọta ọdun ti iṣe, awọn akọrin mẹta ti o tun wa laaye ti ẹgbẹ ti awọn okuta - lẹhin iku Charlie Watts 1886 gbogbo ni awọn Àádọ́rin wọn, tẹsiwaju lati ṣe lori ipele ati ni aṣeyọri ni gbogbo agbaye ati pe ko ṣe afihan eyikeyi ipinnu ti fifi sori ẹrọ..
wikipedia
yo
kiriku (tí a bí ní Oṣù kejìlá ọjọ́ kẹtàdínlógún Ọdún 2014), tí orúkọ àbísọ rẹ̀ sì jẹ́ Enorense Victory, jẹ́ ọmọ Nàìjíríà, aláwàdà, ònkọ̀wé alátinúdá àti ọmọdé òṣèré .Àyè rẹ̀ kiriku jẹ́ ọmọ Benin láti Edo State..
wikipedia
yo
Òun ni àbúrò Umọ̀dọ́ Boy, tó tún jẹ́ alákòóso rẹ̀..
wikipedia
yo
Òun ni ọmọ àbígbẹ̀yìn nínu àwọn ọmọ mẹ́rin tí òbí rẹ̀ bí.Iṣẹ́ ọnà rẹ̀ kirikú bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ aláwàdà rẹ̀ ní ọmọ ọdún mẹ́rin..
wikipedia
yo
Ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ tàn nígbà tí àwọn fídíò rẹ̀ tàn sí ayélujára pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Instablog9ja àti Tunde edNut..
wikipedia
yo
O kọkọ bẹrẹ iṣẹ rẹ ni Ilu rẹ, Benin City, ki o to ko lọ si Ilu Eko Lagos - ti o jẹ orisun Idanilaraya ti orile ede Naijiria - lati tẹle iṣẹ awada rẹ..
wikipedia
yo
O si ti ni apapọ iṣẹ pẹlu Officer WỌOs ati Cute Abiola..
wikipedia
yo
Iwe-iroyin The sun pe e ni alawada ọmọde ti awọn eeyan feran ju lọ ni Naijiria.ami-eye kiriku jawe olubori fun idije "The Breakout Social content Creator fun odun 2022, ni Net.ng Awards.igbese aye ti re oun, ati egbon re ra ọkọ ayọkẹlẹ meji fun awon obi won mejeeji ni odun 2022, gege bi ami ami ìdúpẹ́..
wikipedia
yo
Ó ní ìdí tí òun fi ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ náà fún àwọn òbí rẹ̀ ní pé èyí tí wọ́n ń lọ ti gbó, wọ́n sì ti ń lò ó fún àìmọye ọdún..
wikipedia
yo
Ati pe o ti pinnu lati ra oko naa nigba ti o ba ti lọwọ.Awon itọkasi 2014 birthsáwọn eniyan alààyè People from Edo StateComedy YouTubereng-language-language YouTube ChannelsNigerian Children, YouTubersNigerian male Actors-Century Nigerian male Actors..
wikipedia
yo
Awon Egba je eka eya Yoruba ni apa iwo-oorun ile Naijiria, opo ninu won ni won wa lati aarin ipinle Ogun ti i se Ogun Central Senatorial District.Apapo ijoba ibile mefa ni o parapọ̀ di ogun Central Senatorial District ni IpinleOgun Ogun..
wikipedia
yo
Ìtumọ̀ àkókò rẹ̀ lè wáyé látara ọ̀rọ̀ ẹgbalúgbo, tó túmọ̀ sí alárìnkiri rìn sinu igbó..
wikipedia
yo
Èyí sì lè jẹ mọ́ ìtàn tó fi yé wa pé àwọn ará Ẹ̀gbá wá láti ìlú-ọba Ọ̀yọ́, sínú igbó Ẹ̀gbá, tí ó sì bí ìlú Abeokuta lónìí..
wikipedia
yo
Àwọn “Ẹ̀gbágbọ́” wà ní ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn Ẹ̀gbá tàbí Ẹ̀gbálódòlódò, tí ó túmọ̀ sí alárìnkiri rìn sẹ́bàá odò, tí wọ́n sì padà gé kúrú sí “Ẹ̀gbádò", èyí tó jẹ́ ẹ̀yà mìíràn ní ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ìtumọ̀ mìíràn tó tún rọ̀ mọ́ ìlú Ẹ̀gbá yìí tún lè jẹ́ Ìrúngbà, èyí tí ń ṣe orúkọ Olóyè tó darí àwọn ará Ẹ̀gbá sí agbègbè tí wọ́n wà lọ́wọ́lọ́wọ́.Ìtàn àwọn ọmọ Ẹ̀gbá tó fìgbà kan wà lábẹ́ ìlú-ọba Ọ̀yọ́ gba òmìnira lẹ́yìn tí Ọ̀yọ́ pín ní ìbẹ̀rẹ̀ Ajeẹ́ńtúrì kọ́kàndínlógún..
wikipedia
yo
Ogun ti won ja pelu awon ara Dahomey, ti won si je olubori latari idabobo ti won ri gba lowo oke Olùmọ lo bi isedale ilu Abeokuta, eyi to tún si "abe òkúta".Egba pin si eka mélòó kan, awon ni; Ake, Owu, oke ona, ati gbára, ọkọọkan won lo ni oba tire..
wikipedia
yo
Lásìkò ìṣèjọba àwọn aláwọ̀ funfun, àwọn aláwọ̀-funfun yìí mọ Aláké gẹ́gẹ́ bíi olórí gbogbo ìletò tó wà ní ẹgba..
wikipedia
yo
Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, oye náà ti di oyè Aláké ti ìlú Ẹ̀gbá..
wikipedia
yo
oye awon oba eka yòókù ni Egba ni Aláké ti ilu Egba, Osile ti oke ona, Agura ti Gbagura, ati Olowu ti Owu.O pọn dandan lati se akosile re pe ilu naa wa ni agbegbe oke Olùmọ tele, ti o wa ni agbegbe àgàgà/Ikẹrẹku ti oke ona, ni Egba..
wikipedia
yo
Jagunna ará itọkọ̀, tó jé òkan lára àwọn olóyè òkè ọ̀nà, ní olú-awo òkè olumọ̀.Ìlú Ẹ̀gbá ni Henry Towokond fìgbà kan gbé, ibẹ̀ sì ni ilé ìwé-ìròyìn àkọ́kọ́ ní orílè-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Abiola, onisowo ati oloselu Akin Fobami, AFUC, Aṣoju ìjo̩ba sí France, Monaco, ati Liberia.
wikipedia
yo
Oloye Olusegun Obasanjo, Aare orile-ede Naijiria lati odun 1999 wo 2007 Chief Ebenezer Ola- Obey-Fabiyi, olorin ati ajihinrere.
wikipedia
yo
Olupinnu Olusegun Oludotun Ransome-Kuti, olórin àti ajà-fẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn.
wikipedia
yo
Oloye Olufunmilayo Ransome-Kuti, Aja-Osa-ọmọnìyàn Reverend Oludotun Israel Ransome-Kuti, Ojiṣẹ Ọlọrun, olukọ ati ọga-agba ile-iwe oṣu kẹrin Kẹrin Ile 1891 wo osu kerin, Ọdun 1955) professor duro-Kuti, Aja-Osafe-oṣere- ati Minisita fun eto-Ilera (30 December 1927 - 1 June 2003) Oloye ShoErnest Shonẹ́kan, Aare Aare (26 August 1993 - 17 November 1993) Prof
wikipedia
yo
Wole Soyinka, onkowe, Aja-ogbin-ọmọnìyàn Chief F..
wikipedia
yo
Williams S.A.n., adájọ́ Adewale Òkè Adekola, Onimọ-ẹrọ, omowe, onkọwe Pastor Tunde Bakare, Adájọ́ ati Pásítọ̀ Mr..
wikipedia
yo
Kọ́láwọlé Banmeke Tunde Kelani Segun Odegbàmí, Afẹyinti Agbabọọlu Dimeji Bankole Asa Bùkọ́lá Elemide, olórin Olu Jacobs, òṣèrékùnrin Shina Peters, olórin Àyìnlá Ọmọwúrà, Olórin Prince Bola Ajíbọ́lá, Adájọ́ Chief Simeon Adébọ̀, Adájọ́ Fela Sowande, olórin Oloye Joseph Òkèhan Ọdun Odunjo, on gbajúgbajà iwe jọjọ lẹ́mọ́ Bse Wọ́n CBN John FAnunu, olórin Femi Kuti, olórin ṣeun Kuti, olórin Magun Kuti, olórin Clarence Peters, adarí orin Orin Ẹ E Idún Edè Dgo, òṣèré Ibi Ibikunle Amoru, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ògùn láti Ọdún 2011 Wo 2019 Olóyè Olúṣẹ́gun Ogun Oodua, on àti olóṣèlú, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ògùn láti ọdún 1999 Wo 2003 K Balogun, òṣèrébìnrin Professor Adego, igbákejì Ààrẹ Ààrẹ World Health Organization (Who) Nígbà kan rí Professor Boba Wause, igbákejì Ààrẹ University of Lagos University of àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ẹ̀ṣọ́ Ikoyi orílẹ̀ Yorùbá kan ni èyí jẹ.Oríkì wọn ẹ̀ṣọ́ ò ríKúsàé a-lérí ikú pógunéọmọ àgbọn tii bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ìjà ...àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìró àti bùba jẹ́ orúkọ aṣọ tí ó wọ́pọ̀ láàrín àwọn obìnrin ẹ̀yà Yorùbá ní apá ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà má a ń wọ̀ ..
wikipedia
yo
Ní ìbẹ̀rẹ̀, aṣọ yìí jẹ́ onípele márùn-ún, lára rẹ̀ ni ìró èyí tí ó tóbi jù lọ tí wọ́n máa ń rọ̀ mọ́ ìbàdí..
wikipedia
yo
Nígbà tí bùba jẹ́ ẹ̀wù tí wọ́n ń máa ń wọ̀ lé orí irọ́..
wikipedia
yo
Wọ́n sì máa ń ro ìpele lé orí irọ́ kí ẹwà ìmúra wọn lè yọ dára dára ..
wikipedia
yo
Láfikún , oríṣìíríṣìí aṣọ èyí tó bá wu ni ni wọ́n lè fi rán ìró àti bùba , ó lé jẹ́ aṣọ òfì , Lèèṣí, Ankara, dàńṣíkí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ .Itọ́ka sí..
wikipedia
yo
Egba Ake, tí a tún mọ̀ sí Ẹ̀gbá Aláké jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ka maraarun ti Ẹ̀gbá pin sí..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀ka yòókù ni Òkè-ọ̀nà, gbára, Owu àti Ìbàrà (ìtàn fi yé wa pé Ìbarà wà lára yéwa, kì í ṣe Ẹ̀gbá, àmọ́ agbègbè Abeokuta ni ó wà báyìí..
wikipedia
yo
Aláké ti ìlú Ẹ̀gbá ní ọba tàbí olórí gbogbo ẹ̀yà Ẹ̀gbá.Àwọn olórí èyí ni àtòto àwọn olórí tàbí adarí Ẹ̀gbá, tó joyè Aláké, láti ọdún 1854àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Aláké ti ìlú Ẹ̀gbá ní orúkọ oyè Ọba ti Ìlú Ẹ̀gbá, èyí tó wà ní Abeokuta, ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní apá ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ẹgba pín sí ẹ̀gbà ejò, òwú, òkè-ọ̀nà, àti gbágudára.Ìtàn sagbúa òkúkẹnu di Aláké ti ìlú Ẹ̀gbá tó kọ́kọ́ jẹ́, ó sì jọba láti ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹjọ, ọdún 1854 wọ ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1862..
wikipedia
yo
Ṣaaju ifisípò rẹ ni ọdun 1846, wọn fi SHọmọye joye Adele fun ọdun kan, láàarín ọdun 1845 wo ọdun 1846..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìpapòdà Ọba òkúkẹnu ní ọdún 1862, Shọmọye padà sórí oyè gẹ́gẹ́ bíi adelé, Ó sì lo ọdún mẹ́rin lórí oyè, láàárín ọdún 1862 wó 1866..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, wọ́n fi ọba Ademola í jọba ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kọkànlá, ọdún 1869..
wikipedia
yo
O joye fún ọdún mẹ́jọ títí tó fi papòdà ní ọjọ́ ọgbọ̀n Oṣù kejìlá, Ọdún 1877..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kìíní oṣù kìíní, ọdún 1878, wọ́n yan ọba Oyèkàn láti joyè Aláké ti ìlú Ẹ̀gbá..
wikipedia
yo
Ó lo ọdún mẹ́ta lórí oyè kò tó papòdà ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejìlá, ọdún 1881..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, wọ́n yan olùwájí sórí oyè ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kejì, ọdún 1885, tí ó sì lo ọdún mẹ́rin.Lèyí ọdún méjì ti ipò-ọba ṣòfò, wọ́n yan ọba OshoKalu sórí oyè ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹsàn-án, ọdún 1891..
wikipedia
yo
Ó joba fún ọdún méje, títí wọ ọjọ́ kọkànlá Oṣù Kẹfà, Ọdún 1898 to papòdà..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹjọ Oṣù Kẹjọ, Ọdún 1898, Ọba Gbádébọ̀ í di Aláké ti ìlú Ẹ̀gbá..
wikipedia
yo
Ó lo ọdún méjì lórí oyè, ó sí Ppapòdà ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù karùn-ún, ọdún 1920..
wikipedia
yo
Leyin ìpapòdà oba Gbadebo ni ọdun 1920, Ọba LaDapo Ademola II di ọba tuntun..
wikipedia
yo
ó jọba fún ọdún méjìlélógójì, àmọ́ ó lo ọdún méjì lẹ́yìn odi, láàárín ọdún 1948 wọ oṣù kejìlá ọdún 1950..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìpapòdà rẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá, ọdún 1962, ipò-ọba ṣòfò fún ọdún kan..
wikipedia
yo
Ni ojo kejila osu kejo, odun 1963, won yan oba Adeade Samuel Gbadebo II sori oye..
wikipedia
yo
Leyin ìpapòdà Adeade Samuel Gbadebo II ni ojo kerindinlogbon osu Kẹwàá, odun 1971, Samuel Oyebade lipede gori oye o joba fun odun mẹtalelọgbọn, titi to fi papòdà ni osu keji odun 2005, eyi lo si mu ki Adedọ̀tun Aremu Gbadebo oye gori oye.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Henry Townsend (tí a bí ní ọdún 1815, tí ó sì kú ní ọdún 1886) jẹ́ Aorihere ti Ijo Anglican ní orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Wọ́n fi àmì-òróró yàn án ní ìlú England, ní ọdún 1842..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó ṣiṣẹ́ níbẹ̀ fún oṣù díẹ̀, wọ́n gbé lọ sí ilẹ̀ Yorùbá.Iṣẹ́ rẹ̀ láti ọdún 1846 wọ ọdún 1867, ìlú Abeokuta ni wọ́n ti ń ṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́ wọn..
wikipedia
yo
Thomas Birch Freeman ní aláwọ̀ funfun àkọ́kọ́ tó wọ ilẹ̀ Abeokuta..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó dé sí ilé Badagry ní ọjọ́ ọ̀wònlélógún oṣù kejìlá, ó ṣalábàápàdé ojise Ọlọrun Henry Townsend, wọ́n sì jọ ṣàjọ̣̀GE ọdún Kérésì..
wikipedia
yo
Látàrí ṣíṣe iṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú Samuel Crowther, tó jẹ́ ọmọ Yorùbá àti Ajíhìnrere ní Ìjọ Àgùdà, Townsend kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ orin inú ìwé ní Yorùbá..
wikipedia
yo
Láti ọdún 1871 wọ ọdún 1872, Henry àti Mrs Townsend jẹ́ ọ̀gá ilé-ìwé àgbà fún ilé-ìwé CMS Female Institution ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Henry Townsend fẹ̀hìntì ní ọdún 1876.Henry Townsend se àtẹ̀jáde iwe-iroyin Yorùbá ní ọdún 1859..
wikipedia
yo
èyí ni ó bí iṣẹ́ àtẹ̀ròyìn jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òun sì ni ìwé-ìròyìn elédè méjì àkọ́kọ́..
wikipedia
yo
Igi agbon ( Cocos NUCìtìjú ) je eya igi ope ( Arewww ) ati eya Cocos kan soso ti o ku..
wikipedia
yo
ohun tí a n pè ní “ agbọ́n ” lè tọ́ka sí gbogbo igi agbọ̀n, kóró èso,tàbí èso..
wikipedia
yo
Oruko yii wa lati oruko "Coco' eyi ti o je oruko Àgùdà atijo ti o tumo si ori, tabi agbari.Awon itọkasi...
wikipedia
yo
Olatunde farom je ojogbon imo Biochemistry ati Molecular Toxi..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ ẹgbẹ Royal Society of Chemistry (frsc) UK, ati Nigerian Academy of Science..
wikipedia
yo
O si tun jẹ ọmọ ẹgbẹ African Academy of Sciences at Academy of toxicological Sciences..
wikipedia
yo
O gboye omowe ninu imo Biochemistry lati Ile Eko giga, iyen Yunifasiti iluIbadan.O je okan gboogi ninu awon onimo toxi ni orile orile ede Naijiria.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ agba bọọlu afẹ̀ṣẹ́ gba ọkunrin ti orilẹ-ede Naijiria ni wọn pe ni Super Eagles,ti wọn ma n ṣe aṣoju orilẹ-ede Naijiria ninu idije bọọlu afẹ̀ṣẹ́ gba kakiri agbaye,ti ẹgbẹ Nigeria football Federation (nff) n se alakoso won..Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Olugbénga Agboọlá ọỌn (tí a bí ní ọdún 1985) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó jẹ́ onímọ̀ èrò èdè kọ̀mpútà àti oníṣirò nlá..
wikipedia
yo
Oun ni oludari ati oga ile-iṣẹ flutterWave.ìpínlè Eko ni a bi agboọRussia..
wikipedia
yo
O kawe gboye mba ni ile-iwe MIT Sloan School of Management..
wikipedia
yo
Kí ó tó dá ilé-iṣẹ́ Fpartter sílẹ̀ pẹ̀lú Ìyìn Ìyìn Aja ní ọdún 2016, ó ṣiṣẹ́ bí í atukọ̀ ẹ̀rọ Kọ̀púl ní ilé-iṣẹ́ Pay, ó sì tún jẹ́ adarí ọjà títà ní ilé-iṣẹ́ google.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ẹ̀gbá Gbagura jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn IPisisórí márùn-ún tí Ẹ̀gbá pín sí..
wikipedia
yo
Ẹ̀ka yòókù ni Ẹ̀gbá Ake, Oke-Ona, Òwu àti Ìbàrà(ìtàn fi yé wa pé apá Yewa ni ìbára wà Lonìí, pé kì í ṣe Ẹ̀gbá, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìlú Abeokuta náà ló wà)..
wikipedia
yo
O je ilu ibile to pààlà pelu ilu miiran, lati mu ki isejoba re ga si.Agura ti Gbagura ni olori ibile ti apa kan ilu Egba..
wikipedia
yo
Lábẹ́ ìṣàkóso rẹ̀ ni a ti rí olórí ìletò méjìléláàádọ́rin, tí orúkọ oyè wọn sì jẹ́ baálẹ̀..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwọ̀n agbára kan náà ni Agura àti Aláké ní, àmọ́ lẹ́yìn ìṣèjọba àwọn amúnisìn, Aláké ní a lè sọ pé ó jẹ́ olórí fún gbogbo ẹ̀ka tí Ẹ̀gbá pín sí.Ìtàn ìlú abínibí tí àwọn Ẹ̀gbá tó wà nínú igbó Ẹ̀gbá, jẹ́ èyí tí àwọn ọmọ Yorùbá tó ṣí kúrò ní ìlú mìíràn wá sí ilé wa..
wikipedia
yo