cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ọba tilẹ̀ ti pàṣẹ fáwọn dongari rẹ̀ pé wọ́n gbọdọ̀ má a so wọ́n, wọn ò sì gbọdọ̀ kúrò láàrín ìlú ..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú ìrònú àti ìtẹríba ni àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta fi kúrò ní ààfin lọ́jọ́ náà .Ní òwúrọ̀ kùtùkùtù ọjọ́ kan, àwọn ọmọkùnrin yìí tajú lójú oorun; orin ẹyẹ abàmì kan ló jí wọn. Wọ́n súrédìde , wọ́n sí fèrèsé ilé wọn láti wo ẹyẹ yìí ..
wikipedia
yo
Nígbà tí ẹyẹ yìí parí orin rẹ̀, ó fò lọ, ṣugbọn àwọn ọmọkunrin yìí dá ké jẹ́ lójúkan ń ibití wọ́n wá; wọ́n sì dúró sí i.Ọ̀tá tajú kán , ó sì rí ọfà ati ọrun kan lẹ́gbẹ́ ibití ẹyẹ náà ti fò kúrò; lẹ́gbẹ́ ibẹ̀ ni , ó rí igba, ati i ọjà ìlú wé kan jájẹ ń ibití ẹyẹ náà ti fò kúrò ..
wikipedia
yo
Àwọn ń ọmọkùnrin yìí sáré lọ síbẹ̀, oníkálùkù mú ohun tí ó jọ mọ iṣẹ́ rẹ̀ , wọ́n sì wọlé lọ .l àìpẹ́ , wọ́n lọ sí ààfin láti lọ rí ọba ; ọba sì pàṣẹ fún wọn pé , ní ọ̀kọ̀ọ̀kan kí wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ohun tí wọ́n fọ́n-nu láti ṣe..
wikipedia
yo
O kọjú sí ọ̀tárun ọ wípé , ‘Ìwọ ta ọfà , kí o sì kan òfúrufú..
wikipedia
yo
Ní kíá Mosa , ọ̀tárun mú ọrun ati ọfà rẹ̀, ọrun tí ẹyẹ yìí ti fi sílẹ̀ , ó jẹ́ ọrun abàmì, kò sí ẹnikẹ́ni tó le è rí , yàtọ̀ sí àwọn ọmọ ìyá mẹta yìí..
wikipedia
yo
Ọ̀tárun mú ọfà rẹ àti ọrun náà , ó ta ọfà, láìpẹ́ ọfà yìí fò lọ, ó sì kan ojú ọrun ..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn èèyàn tó wà níbẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí pàtẹ́wọ́, tí wọ́n sì ń kọrin tí wọ́n sì ńlùlù tí wọ́n sì ń jó , wọ́n wípé a ó rí irú eléyìí rí..
wikipedia
yo
Léhìn náà , Ọba kọjú sí dàáràn, ó ní ‘Ó yà ọ́, dàáràn..
wikipedia
yo
Ó ní láti gun ọ̀pẹ láìsí ìgbà ‘ Akọ̀pẹ mú ìgbà tí ó ti mú wá láti le , eléyìí tí ẹyẹ abàmì náà ti fi sílẹ̀ fún wọn ..
wikipedia
yo
Ó mú ìgbà náà , ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í gun igi ọ̀pẹ ; ó ń sáré gùn ún , ó ń gùn tagbáratagbára..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn eniyan ń tún bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe , wọ́n ńpatẹ́wọ́ .Ọba ti bẹ̀rẹ̀ sí í dá ké sìí, ara rẹ̀ sì bẹ̀rẹ̀ síí balẹ̀ ..
wikipedia
yo
Ó rú u lójú , ‘Báwo ni àwọn ọmọ yìí ṣe le se àwọn ohun abàmì yìí ?’ Ṣùgbọ́n láìpẹ́ , láìjina o kọjú sí àwékun o ní , o ya ọ, mú wa lọ sí etí omi, o ní láti wẹ́ òkun já..
wikipedia
yo
Láàrín ìṣẹ́jú kan, àwẹ̀'kún ṣáájú, gbogbo ìlú sì tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Nigbati wọn dé ibi etí omi, ó kán lu omi, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí i lu wẹ̀ ẹ́..
wikipedia
yo
Ó lawọ́ lọ sókè sódò , láàrin ìṣẹ́jú kan, ó ti lùwé tán ..
wikipedia
yo
Gbogbo ìlú ń pariwo , wọ́n ń hó yèè, wọ́n ńṣe hà! Wọ́n ní a kò rí irú eléyìí rí o..
wikipedia
yo
Ẹnu ya gbogbo wọn, báwo ló ṣe ṣe é? Ìjàpá rò pé kò sí ẹnikẹ́ni tí ó rí òun..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ọ̀kan nínú àwọn dòǹgárì ọba kìí mọ́lẹ̀ , ó gbé , ó ní, ‘Níbo ni ìwọ rò pé ìwọ ń lọ ? Ìwọ ẹranko búburú yìí ..
wikipedia
yo
Ó gbé sí èjìká rẹ̀, gbogbo ìlú sì kọrí sí ààfin ọba..
wikipedia
yo
Àwọn ọkùnrin àdúgbò , wọ́n gbé àwọn ọmọkùnrin yìí sí èjìká , wọ́n ń kọrin , wọ́n ńlùlù , wọ́n ń hó yèǹ, Gbogbo ìlú ńdunnú lọ́pọ̀lọpọ̀ fún ohun ńláńlá tí àwọn ọmọ wọ̀nyí ṣe.Nígbà tí wọ́n dé ààfin , ọba sọ fún wọn wípé , òun fẹ́ bẹ̀ wọ́n pé kí wọ́n má bínú ẹ̀sùn tí òun fi kàn wọ́n ..
wikipedia
yo
Ọba kọjú sí ìjàpá ó ní, ‘Ìjàpá , ẹranko búburú ni o; ẹ̀wọ̀n tí ó fẹ́ kí àwọn ọmọkùnrin yìí lọ , ìwọ ni yíò lọ sí ẹ̀wọ̀n náà..
wikipedia
yo
O wá kọjú sí àwọn ọmọkùnrin n náà ò ní, ‘Mo fẹ́ kí ẹ̀yin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta kí ẹ di olóyè ní ààfin miwádìí
wikipedia
yo
Gbogbo ìlú hó yèkù! Wọ́n ń kọrin , àwọn onílù sì ń lu ìlù, wọ́n ń yọ̀ ; wọ́n sì ń bá àwọn ọmọkunrin yìí yọ̀ fún ohun ńláńlá tí wọ́n ṣe.Ẹ̀kọ́ inú àà nílẹ̀ yìí kọ́ wa pé kí á máa gbé ọmọnikeji lẹ́sẹ̀ yálà níbi iṣẹ́ tabi níbikíbi..
wikipedia
yo
Kí a múra sí iṣẹ́ tí a yàn ìyò ká má kó ẹgbẹ́ kẹ́gbẹ́.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìfáàrà Lórí àlọ́ ni ilẹ̀ Yorùbá, ní ìgbà tí kò tíì sí ètò mọ̀ọ́kọ-mọ̀ọ́ká tí ó wà lóde òní, ọ̀rọ̀ at'ẹ́nu dé ẹnu ni àwọn baba ńlá wa máa ń fi ń ṣe àkọsílẹ̀ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó bá ṣe ..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ , àwọn baba yóo sọ ìtàn fún àwọn ọmọ wọn, nígbà tí irú ọmọ bẹ́ẹ̀ náà bá sì di baba , òun náà yóo sọ irú ìtàn bẹ́ẹ̀ fún àwọn ọmọ tirẹ̀ náà ..
wikipedia
yo
Lára àwọn ọmọ irú àwọn ọ̀rọ̀ at’ẹnu d'ẹ́nu tí a ń sọ ní ìtàn , àrọ́bá àti ààlọ̀..
wikipedia
yo
Ní ojú ewé yìí, ààlọ̀ ni a ó máa gbé yẹ̀wò.ààlọ̀ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn onírúurú ọ̀nà tí àwọn Yorùbá máa ń gbà ṣe ìtọ́ni, ìkìlọ̀, ìbániwí, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ fún àwọn ènìyàn wọn..
wikipedia
yo
Tí ìgbà , ààlọ́ a máa níí ṣe pẹ̀lú ẹranko sí ẹranko, ẹranko sí ènìyàn , tàbí àwọn oun àìlọ́pọ̀ míràn tí aṣẹ̀dá dá sinu ayé, lọ́pọ̀ mọ́lè a maa jẹ mọ́ àwọn tí a kò kó lè fi ojú lásán rí..
wikipedia
yo
Pèpéle tí a gbé ààlọ́ lé jẹ́ igba laelae nígbà tí a gbà gbọ́ wípé ènìyàn àti ẹranko ń sọ èdè kan náà..
wikipedia
yo
Nítorí ìmọrírì òdodo ọ̀rọ̀ pé “Ilé la tí ì kẹ́ṣọ̀ọ́ ròde”, ló fi yé pé kí gbogbo ọmọ Yorùbá kọ́kọ́ ṣe àgbéyẹ̀wò ojúṣe wọn bó bá tọ̀nà, kí wọ́n tó lè kópa tó gúnmọ́ láwùjọ gbogbo olùgbé orílẹ̀-èdè yìí nínú jíjẹ́ ìpè ìjọba.Ipò pàtàkì ni Yorùbá tó àlọ́ sí lágbo nlá lítíréṣọ̀ nípa kíkọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ àṣà..
wikipedia
yo
Ẹ̀dá inú àlọ́ ni apálọ hun àṣà tó fẹ́ fi kọ́ àwùjọ lọ́gbọ́n mọ́ lára..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ, iṣẹ́ tí í fi eré ìwà ọ̀dàlẹ̀, tẹ̀tẹ̀lé, ọgbọ́n àrékérekè, ọgbọ́n ẹ̀wẹ́, ọgbọ́n ìjàǹbá hàn ní apáló ṣáátá ń rán alaba ìjàpá nínú àlọ́ (Babalọlá, 1973). Nígbà tí apálọ bá fẹ́ rán ahun nírú iṣẹ́ báwọ̀nyí, Ó sáábà ń fi ẹ̀dá mìíràn tí ìhùwàsí àti àbùdá rẹ̀ lòdì sí tí alabahun ta ko ìjàpá..
wikipedia
yo
Dípò pé kí apálọ (Olùṣẹ̀dá àlọ́) jẹ́ kí ẹ̀kọ́ tó fẹ́ fi ìtàn inú àlọ́ náà kọ́ àwùjọ hàn ní kíákíá, ó máa ń fún àwọn ẹ̀dá inú àlọ́ náà láyè láti tayọ àmúlò àṣà tàbí ọgbọ́n rere àti búburú, bó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà tàbí ọgbọ́n ti apálọ gbàgbọ́ pé ó wúlò, tó sì fẹ́ fi kọ́ àwùjọ ni yóò pàpà jẹ́ kó borí ọgbọ́n tí àwùjọ lòdì sí, ṣùgbọ́n tó ti fún ẹ̀dá inú àlọ́ náà lọ ní àlọ́tẹ́rùn..
wikipedia
yo
Nígbà tí apálọ náà ń hun ìtàn inú àlọ́ náà pọ̀ mọ́ àwọn olú ẹ̀dá tó lọ, ìjàpá, ẹyẹlé, àná ẹyẹlé, abbl., ó mú kí àwọn olú ẹ̀dá ìtàn méjèèjì, ìjàpá àti ẹyẹlẹ́, máa yí ara wọn sebẹ̀ àti sí poro nípa àmúlò ọgbọ́n..
wikipedia
yo
Bí alabahun ti ń fi ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ tí a mọ̀ ọ́n mọ̀ jẹ́ ẹyẹlé níyà, náà ní ẹyẹlé ń fi ìwà sùúrù àti làákàyè àjàgbára..
wikipedia
yo
Nítorí ẹ̀kọ́ tí àpalọ fẹ́ fi kọ́ àwùjọ nínú àlọ́ náà, pé ‘Akọdá ọ̀rọ̀ kò dà bí ọ̀rọ̀ àdágbẹ̀yìn’, ó fi ayé gba alababá ìjàpá láti kọ́kọ́ fi ọgbọ́n àrékérekè jẹ ẹyẹlé níyà kí apálọ ohun tó wà fún ẹyẹlé láyè láti fi hàn pé bèbè ọgbọ́n kò pin sọ́dọ̀ ẹnì kan ṣoṣo. Lára àwọn ìwà burúkú tí a ti mọ̀ mọ́ Àlàbáhun ìjàpá, tí a sì fún un láyè láti hù tẹ́rùn nínú àlọ́ Òkè yẹn ni ìwà àìṣòótọ́, àìṣetonic, àrékérekè, wọ̀bìà, ojúkòkòrò, ahun, Aṣeriní, àjẹkì, ọ̀kań, àgàbàgebè, òfófó, ìfẹ́ àti ẹnu-jíra..
wikipedia
yo
Gbogbo ìhùwàsí wọ̀nyí àti irú wọn mìíràn ni àwùjọ Yorùbá lòdì sí..
wikipedia
yo
Ìjàpá jèrè ìtìjú nígbà ti ìgbín àna rẹ̀ jèrè ìwà àṣejù..
wikipedia
yo
ni apálọ ti hun erè àṣà ahun ṣíṣe pọ̀ mọ́ ìjàpá àti òjòlá lára ṣùgbọ́n ìjàpá ṣe àmúlò ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ láti jẹ́ òjòlá lọjẹ̀ẹ́; èyí tó fa òwe ‘Ènìyàn ní í kọ́ni pé ká gùn, ènìyàn ni sí i kọ́ni pé ká kúrú.’ Nínú àlọ́ mìíràn ni apálọ ti hun ẹ̀kọ́ àṣà àmúlò ọgbọ́n pọ̀ mọ́ ìjàpá (kótonkan ẹranko) àti Erinmi (tó tóbi jù lọ láwùjọ ẹran inú omi)..
wikipedia
yo
Yàtọ̀ sí àwọn àpẹẹrẹ àlọ́ Òkè wọ̀nyẹn, onírúurú àlọ́ mìíràn tó fi ìbáṣepọ̀ ènìyàn sí ènìyàn àti ènìyàn sí ẹranko hàn ló wà, tó sì wúlò fún ìtanijí sí àṣà tó wúlò fún ìbágbépọ̀ ènìyàn ní àwùjọ..
wikipedia
yo
Nígbà tí Alóyinct apálọ yóò bá fi kádìí àlọ́ náà ni onírúurú ẹ̀kọ́ yóò ti handé.Ọ̀nà àlọ́ àpagbé ìtàkùrọ̀sọ tó ń wáyé láàrín apálọ àti ẹlẹgbẹ́ àlọ́ ní ìbẹ̀rẹ̀ àlọ́ òkè yìí wà ní ìbámu pẹ̀lú àṣà..
wikipedia
yo
Ọ̀nà àtimáaṣe àkójọ àwọn ẹlẹgbẹ́ orin àlọ́ ni ó jẹ́ ìdí pàtàkì kan tó fi í wáyé..
wikipedia
yo
Nígbà mìíràn, apálọ a máa fi àlọ́ àpamọ̀ bíi mélòó kan, aró jíjà tàbí ìmọ̀ bíbú kún bátànì ìtàkùrọ̀sọ bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Ìkádìí Àlọ́ Ìdí àlọ́ mi rèé gbangbalaka Ìdí àlọ́ mi rèé gbangbalaka …’Kò ní ìtumọ̀ kan pàtó ju ète ìfọ̀rọ̀dárà, tó tún jẹ́ ìpèdè tó ya àlọ́ sọ́tọ̀ sí ẹ̀yà lítíréṣọ̀ mìíràn..
wikipedia
yo
Ọgbọ́n àtimu ìtàn dùn náà ni. Onírúurú ọ̀nà èdè ni apálọ máa ń mú lọ láti hun ìtàn inú àlọ́ pọ̀, tó ń mú kí àlọ́ dùn kó sì lárinrin..
wikipedia
yo
Benedict Okey Ìdh jẹ́ onímọ̀-ọrọ-ajé àti oníṣòwò lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó sì ti jẹ́ Ààrẹ àti Alága Ìgbìmọ̀ Àwọn Olùdarí ti African Exya-import Bank (Aftsbank: láti ọdún 2015.Ó ti ṣe àtẹ̀jáde ìwé kan, àwọn ìpìlẹ̀ ti ìṣúná Ìṣòwò Ìṣètò, ó sì ti kọ díẹ̀ síi ju àwọn nkan 35 lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀rọ̀-Ajé, Ìṣòwò àti Ìṣòwò Ìṣòwò Áfíríkà.Èkó bí ìrètíd sínú ìdílé àwọn àgbà àgbà làti NNOLE, ní orílẹ̀-èdè igbo, gúúsù ila-oorun Naijiria..
wikipedia
yo
Móábùh jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti ìjòyè ìbílẹ̀ agbègbè.Dókítà jẹunh di M.Sc..
wikipedia
yo
Oyè nínú ètò ọrọ̀ ajé ọ̀gbìn, tí ó gba ní 1987 àti 1991 lẹ́sẹsẹ, Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, Ilé-Ifẹ̀, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oye, tun ni eto eto-ọrọ ogbin, lati Yunifasiti ilu Ibadan, Naijiria, ni odun 1983.O ni iwe-ẹri iṣakoso ilọsiwaju lati Yunifasiti Kọluta80..
wikipedia
yo
Ni 22 Keje 2018, o jẹ ojogbon ti Iṣowo Iṣowo ati Iṣuna Kariaye nipasẹ Ile-ẹkọ giga Adeleke, Naijiria.ojogbon ọmọ Dokita Envh darapọ mọ Afxbank gẹgẹbi Oluyanjú Oloye ni 1994 ati pe o ni igbega si ipo oludari agba, eto ati idagbasoke iṣowo ni 2007..
wikipedia
yo
Ṣaaju ki o darapọ mọ Afximbank, o jẹ alakoso iwadi iranlọwọ ni ile-ifowopamọ ijabọ-iwowọle Ilu Naijiria lati 1992..
wikipedia
yo
O ti jẹ alakoso igbakeji alakoso tele ni idiyele ti idagbasoke iṣowo ati Ile-ifowopamọ Ile-iṣẹ lati (Oṣu Kẹwa 2008 - Oṣu Kẹsan 2015).igbesi aye ara eni o ti ni iyawo o si bi ọmọ mẹta.itọkasiàwọn Ọjọ́ìbí ni 1961awon eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Ìjàpá wo ara rẹ̀ títí lọ́jọ́ kan pé òun náà yóò gbin igba láti di àgbẹ̀ tó lórúkọ láì ní ìmọ̀ nípa rẹ̀ nítorí pé ọmọdé ń gbin igba àgbà ń gbin ìgbà wọ́n sì ń rí towó ṣe..
wikipedia
yo
alababáhun bá he ọkọ́ àti àdá rẹ̀ ó di oko kan tí ó jìnà sí abúlé rẹ̀..
wikipedia
yo
O gbin ìdí ìgbà kan sibẹ, kò jù bẹ́ẹ̀ lọ,o pada sí ilẹ̀..
wikipedia
yo
Ìjàpá kò padà lọ si oko igbà náà mọ́ titi ọdún fi yi po..
wikipedia
yo
nígbàtí ọdún jọ, Onígbá nka'gba wọ́n gbádùn, wọ́n náwó, Ìjàpá náà bá múra ọgbà ọkọ̀ lọ kí ó lọ kórè oko ìgbà rẹ̀..
wikipedia
yo
Bí o ṣe dé bẹ̀, o ní há! Ìwọ ìgbà burúkú yìí ẹyọ kan lọṣọ, àwọn ẹgbẹ́ rẹ ń ṣọ́ ogun, wọ́n ṣọ́ ọgbọ̀n..
wikipedia
yo
O ma kuku yọ́lẹ̀ ko buru, ọ̀kan náà tilẹ̀ tóbi dáadáa, ng ó gbé ọ tà bẹ̀ ó mú owó wá..
wikipedia
yo
Ẹnu ya ìjàpá nígbàtí ìgbà sọ̀rọ̀ ṣùgbọ́n síbẹ̀ síbẹ̀ ó pinnu láti ta ìgbà náà ni wọ́n ìgbà tó jẹ́ pé òun lòún gbìn..
wikipedia
yo
Kí ó bẹ̀rẹ̀ gbé igbá, àfi gbàá ìgbà fọ́ ó kan ìjàpá ni kò, ìjàpá ṣubú lulẹ̀ yakata..
wikipedia
yo
Kí ó dìde máa sá lọ, ìgbà bá yí tẹ̀lé gìrìgìrì gìrìgìrì, kìtà kìtà, ìjàpá bá ń kẹ́ ẹ gbà mí lọ́wọ́ igbá, ó forin S’ ẹnu péOrin Adélọ́ nl'ahunlélógójìgungun Májagunjagun màréẹ́ o lówó teregùngùn májagungún tereigba ó lẹ́sẹ̀gungun má májagun tere (A)gbogbo ẹranko tó pàdé lọ́nà lo fi ṣe ẹlẹ́yà àyàfi àgbò àgbọ́ nìkan ló ran ìjàpá lọ́wọ́ láti bá kan igbà pa..
wikipedia
yo
Àgbò ṣe bẹ́ẹ̀, ó kan ìgbà pa, tí ó sì fọ́ sì wẹ̀té..
wikipedia
yo
Ìjàpá kọ́ lára àkúfọ́ ìgbà fún àgbò ṣùgbọ́n àgbò kọjále pé òun kò fẹ́..
wikipedia
yo
Àgbàlá oooooo yìí dá lórí ìjàpá ati ẹyẹ àdàbà.gẹ́gẹ́ bí a ṣe mọ̀ mọ̀ pé alágàbàgebè ní ìjàpá, ole àti ọ̀kánjúwà ni pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Àdàbà ni ẹṣin kan tó máa ń gùn kiri tí ìjàpá kò sì ní nǹkankan..
wikipedia
yo
Ìjàpá ronú lọ́jọ́ kan, ó sì gbèrò bí yóò ti ṣe pa ẹṣin àdàbà ..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọjọ́ kan ìjàpá dá ọgbọ́n àlùmọ̀kọ́rọ́yí, ó pa ẹṣin àdàbà ..
wikipedia
yo
Ohun tí o ṣe ni pé o gé orí ẹṣin náà ó bòó mọ́lẹ̀ , ó wá fi ojú ẹṣin síta kí ènìyàn lè máa rí i dáadáa ..
wikipedia
yo
Eléyìí yáa lẹ́nu , kíá ó gbéra ó di ilẹ̀ ọba, nígbà tí ó dé ààfin , ó sọ fún ọba pé òun ti rí ibi tí ilẹ̀ gbé lójú ..
wikipedia
yo
Eléyìí ya ọba lẹ́nu ,ó sì tún bi ìjàpá bóyá ohun tí ò sọ dáa lójú ..
wikipedia
yo
Ìjàpá ni ó dá òun lójú , ó sì tún fi dá Ọba lójú wípé kí Ọba yan àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ pé kí àwọn lọ wo ibi tí ilẹ̀ gbé lójú..
wikipedia
yo
Ìjàpá lọ síwájú tó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní í kọrin báyìí pé;orin ààlọ́ìjàpá ----------------_*—Mo ti rí ibi ilé gbé lójúàgbérìn--------Ohùnibùsùnoṣùwàhálàìjàpá ----------------_*--------—Àtì rí ibi ilé gbé lójú --------_*--------—Ilẹ̀ ni gbogbo wọn ń dà rẹirẹi lọ sí ibi tí ilé gbé lójú..
wikipedia
yo
Bí àdàbà ṣe gbọ́ ohun tí ìjàpá ṣe yìí ni ó sáré lọ sí ibi tí ó bo orí ẹ̀sìn rẹ̀ sí tí ó sì wú kúrò níbẹ̀ lọ sí ibòmíràn kí àwọn ẹmẹ̀wà ọba tó dé ibẹ̀ ,nígbà tí ọba , ìjòyè àti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ dé ibi tí ìjàpá wí ,wọn kò rí nǹkankan , ni ìjàpá bá bẹ̀rẹ̀ sí tú ilé kiri títí kórí ojú kankan, ìgbà yìí ni ọba bínú gidigidi pé ìjàpá pa irú irọ́ tí ó tó báyìí àti pé ó tún da òun láàmú láti wá wo ohun tí kò sí níbẹ̀ ..
wikipedia
yo
Kia ni Ọba pàṣẹ pé ki wọn ó ti ojú Ìjàpá yọ idà , ki wọn si ti ẹ̀yin kìí bọ àkọ̀ ..
wikipedia
yo
Ní àtijọ́, ní ìlú ìjàpá, ìyàn mú gan-an ni, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni olúkúlùkù ń ṣe..
wikipedia
yo
Àwọn ìyàwó kò ní iṣẹ́ míràn àfi kí wọ́n tẹ̀lé ọkọ wọn lọ sóko fún ìrànlọ́wọ́..
wikipedia
yo
Bí òjò kò bá ti rọ̀ tàbí eṣú jẹ nkan ọ̀gbìn, ìyàn yóò bẹ́ sílẹ̀ nìyẹn..
wikipedia
yo
Iyán kan bẹ́ silẹ̀ ni ilú Ìjàpá,ti gbogbo ẹranko ninú ilú bẹ̀rẹ̀ si nkú lọ́kọ́, ẹ̀ẹ̀burúkú lọmọdé àti àgbà..
wikipedia
yo
Wọ́n mú owó dání ṣùgbọ́n wọn kò rí oúnjẹ rà bẹ́ẹ̀ni òjò kò kọ́ rọ̀..
wikipedia
yo
Kìnnìún ti ṣe ọba wọn pe ìgbìmọ̀ rẹ̀ jọ fún àpérò kí ìyàn má baà run gbogbo wọn tán..
wikipedia
yo
Wọ́n fẹnu kò sì pé kí àwọn ọ̀dọ́ lọ́kùnrin àti lóbìnrin máa fa ìyá wọn sílẹ̀ fún pípa jẹ, ó sàn kí arúgbó kú ju òdo lọ.Orin ààlọ́kini j'okùn sílẹ̀ o, àlùjánjánjan, Kíninrin j'okùn sílẹ̀ o, àlùjánjánkìke, Ẹ̀rín pa yẹ̀yẹ́ rẹ jẹ, àlùjánjanjan, ẹfọ̀n pa yẹ̀yẹ́ rẹ́ jẹ, bí àlùjanjan gbogb pa'ẹranko pa yẹ̀yẹ́ wọn jẹ, ajá nìkan ló kù o, Kínirin j'okùn sílẹ̀ o..
wikipedia
yo
Ni igba lailai, aburo iyawo Ìjàpá kan fẹ́ gbé ìyàwó..
wikipedia
yo
Àwọn òbí ọkọ ìyàwó ti fi lè Poti, fọ̀nà rokà, pé onílé àti àlejò wá síbi ayẹyẹ ìgbéyàwó àìrírìn náà..
wikipedia
yo
yánníbo, Iyawo Ìjàpá ti lọ si ilé wọn nigbati ètò igbéyàwó naa ti ku bíi ọjọ́ meje lati lọ ṣe àmójútó, bẹ́ẹ̀ni Ìjàpá ọkọ rẹ gbárùkù tii fún gbogbo ìnáwó tó máa ná..
wikipedia
yo
nígbà tí ìjàpá ṣe tán, ó wẹ́, wọ́n fun ní yàrá kan tí ó kàgún sí ilé oúnjẹ pé kí ó sùn díẹ̀ kó tó di alẹ̀ tí ètò ìgbéyàwó máa bèrè..
wikipedia
yo
Òórùn oúnjẹ títàsánsán inú yàrá yìí kò jẹ́ kí ìjàpá ò lè sùn.Ẹ̀bẹ̀ ni wọ́n ń ṣe lọ́wọ́, bẹ́ẹ̀ni òun gbàdúrà kíkankíkan kí wọ́n sọ̀ ọ́ kalẹ̀ wọnú yàrá oúnjẹ lọ..
wikipedia
yo
bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìyá ìyàwó ìjàpá ti bu ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ òsìkí tí ó ní ẹran ìgbẹ́ nínú àti iyán wá fún ìjàpá, ìyẹn kò tẹ́ ẹ lọ́rùn bíi ẹ̀bẹ tó pọ́n réderède pẹ̀lú epo lórí..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ìjàpá ti jẹun tó yó tán, ó sì ń gbèrò láti jẹ́ ẹ̀bẹ, kété tí wọn sọ̀ ọ́ kalẹ̀ sínú yàrá; ìjàpá ṣọ́ wọn lọ́wọ́ lẹ́sẹ̀ ó sí fìlà rẹ̀ ó bú ebè síi..
wikipedia
yo
Ó sì dé mọ́ orí rẹ̀ bẹ́ẹ̀ni ẹ̀bẹ̀ gbígbóná ń jó lórí..
wikipedia
yo
Ìjàpá yára lọ sí ọ̀dọ̀ àna rẹ̀ pé òun fẹ́ lọ pàrọ̀ aṣọ nílé, aṣọ iṣẹ́ ni òun wọ̀ tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Àna rẹ̀ fẹ́ sìn ín sọ́nà, ìjàpá ni rara kí wọn má ṣe yọnu..
wikipedia
yo
Bí omi ṣe ń yọ́ lójú ni ikùn ń yọ nímú,wọ́n bí pé kí ló dé, ó ní ó fẹ́ tẹ òun díẹ̀ ni..
wikipedia
yo
nígbàtí yóò fi délé ooru ẹ̀bẹ̀ gbígbóná ti bọ́ ìwọ̀nba irun tó wà lórí rẹ̀, ebè kò ṣé jẹ mọ́, irun ti kún inú oúnjẹ náà, orí ti bó fàlàfàlà..
wikipedia
yo
Ìjàpá wo ọgbẹ́ títí, ó sàn ṣùgbọ́n irun kò wú níbẹ̀ mọ́..
wikipedia
yo
Èyí ma ń jẹ́ kí Ìjàpá tọrọ omi lọ́wọ́ alákàn nígbà ẹ̀ẹ̀rùn tàbí tí òjò kò bá rọ̀..
wikipedia
yo
Ìjàpá a máa jowú alákàn, inú a máa bíi, ó sì ń wọ̀nà a ti pa alákàn l'ọmọ..
wikipedia
yo
Nígbà kan, iyàn mú ni ìlú ìjàpá, kò sí ọjọ́ gbogbo odò kékèké ti gbẹ..
wikipedia
yo