cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ìṣẹ̀lẹ̀tó Jephthah Oluwatiṣeyiẹsẹ̀ Tanimọ̀la ti inagijẹ rẹ nje Akpororo jẹ alawada ati osere lọkunrin ile Naigiria.igbesi aye arakunrin Naapororo ni a bi tòsí dàgbà sí Warri ní Ìpínlẹ̀ Delta ṣùgbọ́n tó wá láti Ìlàjẹ, Ìpínlẹ̀ Òndó..
wikipedia
yo
Irin ajo arakunrin naa bẹrẹ gẹgẹbi olorin ni ọdun 2008 nibi to ti pegede ninu idije Zone ti Calabar.
wikipedia
yo
Ni 2009, Akpororo losi Eko tòsí kopa ninu idije nibi tótí se ipo keji..
wikipedia
yo
Ni osu August, odun 2014 arakunrin naa bere awada re akoko Akpororo VV Aksororo ni Hall ti Shell ni MUSON Centre.Ni odun 2014, Aksororo bẹrẹ irin ajo gegebi osere lọkunrin ninu fí53 headGone ati antiquepororo fe Josephine Ijeoma Abraham ni Surulere, Ipinle Eko ni ojo kerinla osu November, odun 2015.Ekosororo Keeko ni ile iwe giga ti Ipinle Eko lori imo sociology.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Chuks d General ti orúkọ a bísọ rẹ̀ njẹ́ dágannu Jude Israel jẹ́ aláwàdà, host, Radio Presen àti òṣèré lọ́kùnrin..
wikipedia
yo
Chuks jẹ́ olùdarí show tí ìtara tó kọ́ àwọn gbajúmọ̀ ilẹ̀ Naigiria jọ lórí ìdánitsks ní oje aláwàdà tó pegede jùlọ ní Abuja.Òṣèré lọkunrin naa dá "Official couple" sílẹ̀; eré Oritage náà ṣe àfihàn ìgún Lecky(ara àwọn tó kópa nínu ìdíje Big Brother Naija).Ìgbésí ayé arákùnrin náàks d General ni a bini ọjọ́ mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n, Oṣù February ní AGBOR, Ìpínlẹ̀ Delta.Ní ọjọ́ kẹrìnlélãgun, Oṣù August ní ọdún 2019, Chuks fẹ́ Ngozi tó wá láti Ìpínlẹ̀ Anámbra.Èkó losi ilé ìwé ti Staff Model ní AGBOR, Ìpínlẹ̀ Delta..
wikipedia
yo
Arákùnrin náà jáde ní ilé ìwé gíga ti Ìpínlẹ̀ Nasarawa níbi tó ti kẹẹ̀kọ́ lórí ìmọ̀ statistics...
wikipedia
yo
Ni ayé àtijọ́ , òkèrè àti Ìjàpá jẹ́ ọ̀rẹ́ ẹ̀ kò-ri-kò- sùn, wọ́n fẹ́ràn ara wọn lọ́pọ̀lọpọ̀..
wikipedia
yo
Ọwọ́ kan náà ni wọ́n jọ ń ṣe, awọ ni wọ́n ń ta , ibi kan náà ni wọ́n sì pa òfo sí..
wikipedia
yo
Oníṣòwò awọ ni Asin naa , Asin àti Ọ̀kẹ́rẹ́ wọn jọ wà ni ẹ̀gbẹ́ ará wọnnì ọjà ti Ìjàpá si ta kété si wọn.Ni ọjọ́ kan, Ọ̀kẹ́rẹ́ pé lọ s'Ọjà, Ìjàpá ló n dúró de nitori pé Ìjàpá kò lè rin kánmọ́-kánmọ́..
wikipedia
yo
asín ti ru àwo tiẹ̀ dé ọjà , àwọn oníbàárà rè tí ń rà á wìtìwìtì kí ọ̀kẹ́rẹ́ tó dé..
wikipedia
yo
Ìgbà ti òkèrè dé , ohun náà tó’gba tirẹ̀ , ṣùgbọ́n eṣinṣin ni yọ owó imí ..
wikipedia
yo
Inú bẹ̀rẹ̀ síni bí òkèrè , bẹ́ẹ̀ni ní òkèrè bẹ̀rẹ̀ sini da gbogbo nkan rú, ó si ń kọrin òwe, ó n sọ oko si Asin, Asin kò si da lohun..
wikipedia
yo
Ní ìgbà tó yá ,ọmọ tí asín gbé wá sí ọjà ,ọmọdé náà ti bẹ̀rẹ̀ sí nìí rà,asín sì sọọ́ kalẹ́ nígbà tó nta jà fún àwọn oníbárà rẹ̀ ,ọmọ yìí ń rà kiri, ó ń ṣeré..
wikipedia
yo
Nígbà tí ọ̀kẹ́rẹ́ pa àtẹ awo rẹ̀ kálẹ̀, ọmọdé yìí rá lọ sí ibẹ̀ ó fi ọwọ́ kan ọ̀kan nínú àwo, ara ti kan aláwọ̀ yìí nígbà tí òun kò tà, ìyá ọmọdé yìí ló ń ta látàárọ̀ ,tìkanra tìkanra ló fi gba owó ọmọdé yìí ,tó já àwọ̀ rẹ̀ gbà, tó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní bu ìyá ọmọ yìí ní mẹ́sàn án mẹ́wá ..
wikipedia
yo
asín gbìyànjú láti fún òkèrè ní sùúrù ṣùgbọ́n etí òdì ló fi ń gbọ́ gbogbo àlàyé asín, báyìí ni asín pẹ̀lú òkèrè bẹ̀rẹ̀ sí ní ta ipòrógàn..
wikipedia
yo
wọ́n n bú ara wọn ní abojú àbòmú láìpẹ́ àwọn méjèèjì kọlũ ara wọn,wọ́n fi ìjà pẹẹ́ta..
wikipedia
yo
asín kò lágbára tó òkèrè tẹ́lẹ̀, èrò pé òun yóò fìyà jẹ asín ló wà lọ́kàn òkèrè tó fi sọ ọ̀rọ̀ di ìjàkadì ..
wikipedia
yo
Ẹsẹ̀ ń kú bí òjò ,ariwo ń sọ gèè,wọ́n fọ́ awọ ara wọn,àwọn kan ń wòran ,àwọn kan ń la ìjà nígbàtí àwọn kan ń dá kún ìjà ..
wikipedia
yo
ìròyìn kan Ìjàpá lára pé Asin àti Ọ̀kẹ́rẹ́ n jà, igi ni Ìjàpá fàyọ,gẹ́gẹ́ bi àti mo pè ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ Ìjàpá ni Ọ̀kẹ́rẹ́ , ti ó bá ná òkèrè ní igi kan, mẹ́wàá ni yóò na Asin , nigbà ti Asin ri wípé Ìjàpá kò là wọ́n ni ijà , ijà ọ̀rẹ́ rẹ Ọ̀kẹ́rẹ́ ló n gbé ti ọwọ́ rẹ si le ju Ọ̀kẹ́rẹ́ ti òun n bá jà lọ,Asin fi Ọ̀kẹ́rẹ́ silẹ̀ ó si toro mọ́ Ìjàpá ó dè yín dé ni igi imú, ẹ̀yìn Asin wọlé ṣinṣin, ẹ̀jẹ̀ n ṣàn ewé lati igi imú Ìjàpá ..
wikipedia
yo
Ó ké pe èrò ọjà kí wọ́n gba òun lọ́wọ́ asín ó f’orin sí, ó ń pe;orin Àlàó Asin t'óun t'ókù jọ̀ọ́ mi jọ àwọn ni wọ́n jọ ń já jọ̀ọ́ mi jọìjà rèé mo wá la jọ̀ọ́ mi jọ asín bu mi nímú jẹ jọ̀ọ́ mi jọ ẹ gbà mí lọ́wọ́ rẹ̀ ó jọ̀ọ́ mi jọ àwọ̀ mi ń bẹ lọ́jàj mi jọìjàpá àti gbogbo àwọn èrò tí ó wà ní ọjà bẹ̀rẹ̀ sí níí bẹ asín ọ̀kẹ́rẹ́, gan ń bẹ asín ṣùgbọ́n tí asín di ojú pin tí kò sì fi ìjàpá sílẹ̀ títí tí imú ìjàpá fi já mọ́ lẹ́nu báyìí,báyìí ni àwọn ènìyàn bẹ̀rẹ̀ sí níí dá ìjàpá lẹ́bi wípé kò la ìjà náà ní túbi-n-nu-bí, wípé ìjàpá ńṣe ojúṣaájú láàrin wọn,láti ìgbà náà ni imú ìjàpá ti kú Kanmbo. Olùlọ́ àààbọ̀ yìí kọ́ wa pé kò yẹ kí a máa la ìjà àbòsí , bí oníwó bá ń já, ọtun ló yẹ ká dá lé kún kún ,a kò gbọdọ̀ f mọ́ ẹnìkan ká máa na ẹni kejì o, Ọlọ́run má jẹ́ kí ọ̀ràn dí an o o..
wikipedia
yo
Àṣé Èdùmàrè .Ìdí ààlọ́ mi rẹ̀ gbangbalakaìdí lọ́àbọ̀ mi rèé gbangbabí ng bá parọ́,kí agogo ẹnu mi má ó bí ng ó bá parọ́,kí agogo ẹnu mi ro lẹ́ẹ̀mẹ́taó di pó......pọ̀..
wikipedia
yo
PAR ìjàpá àti yánníbo Aya re ààlọ̀ O!! ààlọ̀! ààlọ̀ mi dá fírí, ó dá lórí ìjàpá àti yánníbo aya rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìjàpá fẹ́ ìyàwó rẹ̀ nígbàtí ó pé ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n..
wikipedia
yo
Ọ̀nà rẹwà pupọ l'obinrin, ó pupa fòò, ẹ̀yin ẹnu rẹ̀ funfun nigín nigín Dada..
wikipedia
yo
Ìyàwó ìjàpá síngbọnlẹ̀, kò sí ohun tí ó wọ̀ (bíi aṣọ, bàtà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ) tí kò níí yọ ní ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀nà rẹ'wá lóòtọ́, bẹ́ẹ̀ ni ó tún fi ìwà tútù bíi àdàbà kún ẹwà rẹ..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n yánníbo kò ri ọmọ bi, ọmọ bibi ṣe pàtàkì ni ilẹ̀ Yorùbá, nítorí eyi Ìrònú ma mba ti o ba ri obinrin ti kò bá ri ọmọ bi tabi ti o ya Àgàn. Yáníbo kò dúró lásán, ó tọ babaláwo lọ lati ṣe àjọ bi ohun ti le ri ọmọ bi..
wikipedia
yo
Babaláwo se àṣejẹ fún Yáníbo, ó rán ìjàpá lati lọ gba àsàjẹ yí lọ́wọ́ babaláwo. Babaláwo kilọ̀ fún ìjàpá gidigidi wípé ogun yi, obinrin nikan ló wà fun, pe ki ó máṣe tọwọ́. Ìjàpá ọkọ Yáníbo ṣe àìgbọràn, ó gbọ́ orun àṣejẹ, ó tọ́ wò, ó ri wípé ó dùn, nítorí ìwà wobí ọ̀kánjúwà, ó bá jẹ́ àṣejẹ tí babaláwo se ikilọ kí ó pamí..
wikipedia
yo
Ọbafẹ́mi làsóde (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrin oṣù Kejìlá ọdún 4 1955) jẹ́ gbajúmọ̀ olórin, olùdarí àti olóòtú sinimá , ó jẹ́ òǹkọ̀wé àti olóòtú orin, eré-oníṣe ọmọ Nigeria..
wikipedia
yo
Oun ni Oludari-Agba Ile-iṣẹ Even-Ezra Nigeria Limited, ti o se agbateru sinima olokiki ni, Sango ti o gba opo ami-eye lodun 1997.igbesi-aye re lati iberewon bi Obafemi Bándélé Lfun lọjọ kerin osu kejila odun 1955 ni ilu Port Harcourt, olu-ilu Ipinle Rivers lórílẹ̀-ede Nigeria, sugbon ti awon obi re je omo bibi Abeokuta, ni Ipinle Ogun..
wikipedia
yo
Gregory’s College ní ìlú Obalende ní ìpínlẹ̀ Èkó, níbi tí o ti kàwé gbàwé ẹ̀rí West African Senior School Certificate..
wikipedia
yo
O tẹsiwaju ninu ẹkọ rẹ ti o si kawe gbawẹ ẹri Bachelor of Science ninu Imọ Business Administration ni Ile Eko KoGod School of Business, ni ilu Washington, D.C..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó tún kàwé gbàwé ẹ̀rí Master of Science nínú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ìbánisọ̀rọ̀, Communication Art láti Brooklyn College, City University of New York.Iṣẹ́ ò dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ Inner City Broadcasting Corporation, ti ìlú New York City lọ́dún 1983 gẹ́gẹ́ bí olùdarí ìpolongo, níbi tí ó ti gba Sonny Okoìtọ́jú lálejò lọ́dún 1984 ni gbajúmọ̀ Gbọ̀ngàn Àgbáyé ni, Apollo Theater ní Harlem.Ó ṣe agbátẹrù ètò orin Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Áfíríkà tí a mọ̀ sí Áfríkà in Vogugue lórí pẹpẹ Radio Nigeria 2, ètò yìí bẹ̀rẹ̀ lọ́dún 1989, tí wọ́n sì ṣe é fún odidi ọdún kan gbáko..
wikipedia
yo
In 1995, he established Afrika 'n Vogue/Even-Ezra Studios.lodun 1997, o se agbateru ati oludari sinima kan gboogi ti o gbàmí eye kaakiri ile Adulawo Afirika ti akole re n je Sango, gbajumo sinima ti won yan lati Side ajọdun Minneapolis-Saint Paul International Film Festival lodun 2002..
wikipedia
yo
Adegboyega Dosunmu amọ́roro II (CON) jẹ ọba ile òwú ni Ipinle Ogun, ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ó gun orí oyè yìí nígbà tí Ọba Olawale Adisa Odelẹyẹ, Llàgbẹ̀ I Wàjà ní Oṣù Kẹfà Ọdún 2003 ní ẹni ọdún márùn-dín-ìOṣù.Ọba Adegboyega Dosunmu jẹ́ ọmọ bíbí inú òjí'ọba Benjamin Òkènà Dosunmu (ọ̀kan lára àwọn ọmọ oyè ní ìran olóògbé ỌBA Adesun Dosunmu, Amororo Kínní) ẹni tí ó joba láàarín ọdún 1918 àti 1924) ní ilẹ̀ Owu..
wikipedia
yo
Benjamin Okelànà Dosunmu yìí ni ọmọ kẹta tí Ọba Adesunmbo Dosunmu, Amororo í bí..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ ìwé rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Ijo Onítẹ̀bọmi ní Owu (Owu Baptist Day School), Abeokuta ní ọdún 1941..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ girama ti àwọn Baptist Boys’ High School, níbẹ̀ ni ó sì ti gba ìwé ẹ̀rí oníwèé mẹ́wàá ní ọdún 1950..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú nínu ìwé kíkà rẹ̀ nígbà tí ó lọ sí ìlú Òyìnbó láti lọ gba ìmọ̀ lórí eré orí-ìtàgé àti bí a ti ń ṣe ètò orí ẹ̀ro-Amóhùn-máwòrán Drama and Television Production ní ilé ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ (Hendon College of Technology) ní ìlú Ọba (London) ní ọdún 1963..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó tún tẹ̀síwájú láti lọ sí ìlú Amẹ́ríkà láti lọ kọ́ ẹ̀kọ́ nípa ẹ̀sìn ìgbàlódé ní ilé-ẹ̀kọ́ ìjọ onítẹ̀bọmi tí ó wà ní ìlú Tennessee (landMark Baptist College Tennessee, USA) níbẹ̀ ni ó ti gba oye ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì ní ọdún 1987.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ademola Nurudeen Jackson Adeleke (Ọjọ́ìbí 13 May 1960) je oloselu ati onisowo Naijiria kan, eni ti o ti se gomina ipinleOsun lati odun2022..
wikipedia
yo
Oun ni Senéto to ṣoju agbegbe Senatorial Osun-West lati 2017 si 2019..
wikipedia
yo
O dije ninu idibo gomina ipinle Osun lodun 2022 labẹ ẹgbẹ oselu Peoples Democratic Party, o si bori gomina to wà níbè, Adegboyega Isiaka Oyetola ti ẹgbẹ oṣelu APC ti o jáwé olubori ninu ibo Gomina Ipinle Osun lodun 2018 .Eko Adeleke beere Eko akọ bẹrẹ ni Methodist Primary School, Surulere Lagos State ki o to pada si ìlú Oyo State lati tẹsiwaju ninu Eko ni NAwakirudeen Primary School, Ikire..
wikipedia
yo
àti ilé ìwé Èkó gíga Seventh Day Adventist Secondary School, èdè ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti ka ìwé ní èdè Muslim Grammar School Ede, níbití tí ó ti parí Secondary School Education láti lọ ka ìwé ní ìlú United States.[3] Ó fi ìlú Nigeria láti lọ ka ìwé pẹ̀lú àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ méjì ní United States of America.[3] Ìwé ẹ̀kọ́ gíga ní Jacksonville State University,[4] Alabama tí ó sì gboyè degree..
wikipedia
yo
Nipa odaran ati oselu.[5]Awon ise aladaniAdeleke je onisowo ati Alákọ̀wé, O sise gege bii alakoso agba ni ile-ise ìpọntí Guiness lati odun 1992 si odun 1999 nibiti ikan ninu awon akegbe re si je oga-ogun Theophilus Danjuma; o tun je alakoso agba ni ile-ise aburo re, Pacific Holdings Limited lati odun 2001 titi di odun 2016..
wikipedia
yo
Kí ó tó dára pọ̀ mọ́ Pacific Holdings Limited, ó ti ṣiṣẹ́ ní Ilé Iṣẹ́ Ìfi Nǹkan ránṣẹ́ tí a mọ̀ sí QuilSilver Courier Company ní ìlú Atlanta, Georgia ní Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà gẹ́gẹ́ bí àgbà iṣẹ́ ṣe ní ọdún 1985 sí ọdún 1989..
wikipedia
yo
O tẹsiwaju ri ile-iṣẹ awon nǹkan olóorun àdídùn ti a mo si Origin International LLC ni Ilu Atlanta ni Georgia ni orile-ede Amerika gege bi Igbakeji Alakoso Agba patapata lati ọdun 1990 si ọdun 1994.itọkasi..
wikipedia
yo
Tẹjú babyface ni tún pé ní Gbadewọnúọlá Ọlátẹ́jú Ofojúgú tó jẹ́ aláwàdà àti Ìkọ̀wé ilẹ̀ naigiria
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nairia ma n pe arákùnrin náà ní “Ọba sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀"Ìgbésí ayé arákùnrin náàja Babyface ni a Bìní ọjọ́ ogún osu January, Ọdún 1979.Ni ọdún 1999, arákùnrin náà bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn tó kópa nínú eré àgbéléwò tí olùdarí Tádé Ògìdán “Diamond King”
wikipedia
yo
Ní ọdún 2001, tẹjú kópa nínu eré àgbéléwò "One Too Much".ní Ọdún 2010, OyeÌyànkun dá "Tẹjú Babyface Show sílẹ̀ tó sì ti gbàlejò oríṣiríṣi àwọn èyàn jàkàn jàkàn.Ní ọdún 2017, wẹ́́n ní a fi jẹ́ Ambassador ti United Nations Sustainable Development Goals.ní Oṣù September Ọdún 2012, OyeÌyànwe fẹ́ Olúwatóbi Banjókò.O.ní ọdún 2018 ni wọ́n bí ìbejìní.
wikipedia
yo
ààlọ̀ Oìjọbaìjọba mi dá fírítàbí, ó dá lórí ìjàpá àti àparò..
wikipedia
yo
Go! Je jara ti ere idaraya Ara Amerika-Kánádà.Àwọn oṣere Michela Luçi gẹgẹ bi Tag tira Callum Shoniker gege bi Scooch Pooch Katie Griffin gege bi Ma Bara Martin Julan gege bi Paw Gbaja Tajja ìṣẹ̀ǹbáyé gẹgẹ bi Seti Biscuit / Franny's Mom / Beefste Beey Lyon Gẹ́gẹ́ bi Spike Onike Judy MarShank Gẹ́gẹ́ bi Grandma Marge Funra / OyOnes Patrick McKenna Gẹ́gẹ́ bi Grand1978 Mo tira / Gerald / Mutt / Man Doghole / Brutus Linda Ballanne gẹ́gẹ́ bi Lady Lydia / SGTfin Toch / Mayor SYẹ Joshua Graham gẹ́gẹ́ bi Sam O Lè Franny's Dad's Yẹ Bernard Rubber Deven Mack gẹ́gẹ́ bi La- David Berni gẹgẹ bi Frank an MojaraM gẹgẹ gẹgẹ bi Be / flip Chasely / Firan Dog / Bow / Kínní John Stocker gẹgẹ bi Leo How Leri Eeu from lati catch Morely Paul Ju Vley, Rels Ṣe Zod d' àti bi The Bar Barkinillas 2003 Gẹ́gẹ́ bi tòótọ́ Chew /man Ga Roof Robert Robert tin gẹgẹ bi early ed Jamie Watson Gẹ́gẹ́ bi Donny S de Annru de La bi Sandra PA Man TW lati 2017 gẹ́gẹ́ bi Ben Kay Gẹ́gẹ́ bi Kelly A S a R Wa bi wind O 2016 Rocha Gẹ́gẹ́ bi Kit Whiston Paulton Braun Gẹ́gẹ́ bi Tom bi Tomtonton (to To gẹgẹ bi Big Dogtie Haila (g gẹgẹ * ***Lo ode 2..
wikipedia
yo
Articles with HcardsHaley lu Richardson (ti a bi ni 7 March 1995) jẹ oṣere ara ilu Amẹrika kan..
wikipedia
yo
Ni atẹle awọn ipa tẹlifisiọnu ni kutukutu lori Disney Channel sitcom Shake It Up (2013) ati eré elere ABC Family Ravenswood (2013 – 2014), o ṣe ni fiimu ti n bọ ti ọjọ-ori The Edge of Seventeen (2016) ati fiimu ibanilẹ ọpọlọ Pipin (2016).Richardson ni ipa Breakut rẹ ninu ere ominira Columbus (2017) fun eyiti o gba aami eye fiimu Independent Goham fun yiyan oṣere ti o dara julọ ..
wikipedia
yo
O tẹsiwaju lati farahan ni awọn fiimu ominira ti o ni iyìn gẹgẹbi atilẹyin awọn ọmọbirin (2018), UNpregnant (2020), ati lẹhin yang (2022)..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2022, o ṣe irawọ ninu jara anthology HBO the White Lotus (2022).igbesi aye ibẹrẹ Haley Lu Richardson ni a bi ni Phoenix, Arizona, Ọmọbinrin Valerie, Óun ati alamọja iyasọtọ, ati FORT L..
wikipedia
yo
Richardson lọ si Villa Montessori nipasẹ ile-iwe arin, lẹhinna ile-iwe giga ArcAdia ..
wikipedia
yo
O jẹ deede ni awọn iṣelọpọ iṣere ati awọn idije ijo agbegbe jakejado iwọ oorun guusu..
wikipedia
yo
Lati ọdun 2001 - 2011 o jẹ onijo asiwaju ni Ile-iṣẹ Dance CNedy ti Phoenix..
wikipedia
yo
ní ọdún 2011, ó gbe lọ si Hollywood, California.Iṣẹ-ṣiṣe ni 2013, Richardson bẹrẹ ipa loorekoore bi Teess ninu jara idile ABC Ravenswood ..
wikipedia
yo
ó ti farahàn bí àlejò lórí Disney Channel ’s shake it up àti pé ó jẹ́ ìràwọ̀ kan ní iṣelọpọ àwaoko ABC ti “ti gbà..
wikipedia
yo
O ṣe Juliana ni igbesi aye atilẹba fiimu abayo lati ilobirin pupọ, lẹgbẹẹ Jack Falahee ..
wikipedia
yo
ní ọdún 2016, ó ní ipá lóòrèkóòrè bí Elie ní ọ̀nà eré ìmúláradá Freeform ..
wikipedia
yo
iṣẹ́ fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ pẹ̀lú ipá aṣíwájú nínú àwọn ìyókù tí ó kẹ́hìn àti àwọn iṣẹ́ àtìlẹ́yìn ni Edge ti Seventeen àti pípín ..
wikipedia
yo
Aṣeyọri rẹ wa ni ọdun 2017 nigbati o ṣe irawọ idakeji John Cho ni Columbus ..
wikipedia
yo
Fun ise re ninu fiimu o je yiyan fun 2017 Goham Independent Film Award fun osere ti o dara julo..
wikipedia
yo
Ninu fiimu o se alaisan Cystic FIBrosis ti o ṣubu ni ife pẹlu ọmọkunrin kan ti o ni arun kanna..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2022 o ṣe irawọ bi Portia ni akoko keji ti awada anthology HBO the White Lotus .igbesi aye ara eni Richardson ti n Crocheting lati ọdun mẹjọ, ati pe o ni ile itaja EIndus nibiti o ti n ta awọn ẹya ẹrọ ati awọn aṣọ Crocheted ti a ṣe lati awọn aṣa tirẹ.Fiimu-tẹlifisiọnuàwọn itọkasiita ìjápọ awọn Ọjọ́ìbí ni 1995àwọn Eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
5460 Tsenààt'a'i jẹ́ plánẹ̀tì kékeré ní ibi gíga ọṣẹ́ìdí.Ìtọ́kasí àmúyẹìdí)".
wikipedia
yo
jẹ́ plánẹ̀tì kékeré ní ibi gíga ìrúbọìdí.2 ..
wikipedia
yo
Àgbàlá oooo lọ́lọ́ mi dá fírígbàgbọ́ ó dá lórí ìjàpá àti àwọn ọmọ òrukàn mẹ́ta kan..
wikipedia
yo
Ní ìgbà láéláé, àwọn ọmọ òrukàn mẹ́ta kan wà tí orúkọ wọn ní jẹ́ ọ̀tárun, jàkà, àti awẹ̀kun.Àwọn ọmọ yìí pinnu láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ọwọ́, láti ìgbà tí òbí àwọn ọmọ yìí ti kú, ìjàpá máa ń tọ́jú wọn, ó sì máa ń gbà wọ́n ní ìyànjú lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
nígbà tí wọ́n dé ibẹ̀ wọ́n kí, òun náà sì kí wọn dáadáa ..
wikipedia
yo
Ó fún wọn ní òbí, gbogbo wọn sì jókòó ní abẹ́ igi níwájú ilé rẹ̀ .Ọ̀tá ni ó kọ́kọ́ sọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Ó ní, ‘Èmi àti àwọn àbúrò mi fẹ́ níláti dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ gidigidi ìjàpá , fún akitiyan rẹ lórí wa látìgbà tí àwọn òbí wa ti fi ayé sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ohun tí a mú wá sọ́dọ̀ rẹ̀ lónìí ni wípé àwa fẹ́ kí ó gbà wá níyànjú nípa ọ̀rọ̀ ìṣe ..
wikipedia
yo
A fẹ́ láti lọ kọ́ iṣẹ́ .Ìjàpá mi kanlẹ̀ , ó wọ òkè ó wọ ilé ..
wikipedia
yo
O ní ẹ ṣeun, mo dúpẹ́ lọ́wọ́ yín wípé , ẹ ò fojú di àgbà..
wikipedia
yo
Èmi yóò sì gbà yín níyànjú wípé kí ẹ wá bá mi da owó pọ̀, kí ẹ wá bá mi ṣe iṣẹ́ pọ̀.Àwọn ọmọkùnrin mẹ́ta yìí wo ojú ara wọn..
wikipedia
yo
Akọ̀pẹ dáhùn pé , ‘Ìyẹn ni wípé oníṣòwò ni ìwọ ìjàpá, àwa kò mọ̀.ìjàpá rẹ rìn ó ní , ’oníṣòwò ni mí..
wikipedia
yo
Ẹ kò ṣe akiyesi pé nkò ni oko, nkò sì ni abà; èmi kì í sì í ra ọjà, ńkì í sì í ta ọjà..
wikipedia
yo
Ṣugbọn, mò ń jẹ , mò ń mu láìṣe aláìní ohunkohun.Àwọn ọmọ ìyà yìí tún wo ara wọn tìyanutìyanu, wọ́n sì tún wo ìjàpá tìfuratìfura..
wikipedia
yo
Ìjàpá dáhùn ó ní , ‘Kílódé tí ẹ fi ń wò mí bíi ẹni pé mo gbé idà sókè láti fi bẹ̀ yín lórí? Ṣé ẹ rò pé alọ́nilọ́wọ́gbà ni mí ni? Èmi kì í ṣe jàǹdùkú o..
wikipedia
yo
Ó kàn jẹ́ pé ohunkohun tí mo bá fẹ́ , n ó rí gbà.Àwọn ọmọkunrin yìí kò mọ ohun tí wọn ò fi fèsì..
wikipedia
yo
Lẹhin isẹju diẹ, ọtarun dide o ni, 'Àwa yio lọ ro ọrọ ti o fi lọ wa wò, awa yio si fesi bọ ba d'ọ̀lá'.Ní ọjọ́ kejì, Okoni nikan lọ lọ si ilé ìjàpá , o si wi fun pe, 'Ẹmi ati aburo mi ti ro ộrộ ti iwọ lọkà wá, a si dúpé lọwọ rẹ fun imọran naa, ṣùgbọbo a ko le ba ọ sise,nítorí pe olótìítọ́ eniyan ni awa, a fẹ lati fowo wa se iṣẹ àṣeka..
wikipedia
yo
Inú bí ìjàpá púpọ̀ , ojú rẹ̀ sì pọ́n, ó ní ,aláìmoore ni ẹ̀yin ọmọdé wọ̀nyí, ṣe ohun tí ẹ ó fi san oore láti ìgbà ìtàWỌWỌobìbíiy ti àwọn òbí wọn ti jáde kúrò láyé nìyẹn?’Ọ̀tá dáhùn ó wípé , ‘Bẹ́ẹ̀ ni,“”“
wikipedia
yo
Ìjàpá sì wí fún wípé , Bí ó bá wá rí bẹ̀ ọ́, èmi ìjàpá ti di ọ̀tá yín, èmi ó sì fi ojú yín rí èèmọ̀ lẹ́hìn ọ̀sẹ̀ díẹ̀, àwọn ọmọkùnrin náà bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ iṣẹ́ ọwọ́, wọ́n sì ṣiṣẹ́ kárakára..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe iṣẹ́ wọn láṣẹ yọrí ; láìpẹ́ ọ̀tárun bẹ̀rẹ̀ sí ṣiṣẹ́ ọdẹ, ó sì ṣeé ó ní òkìkí nínú iṣẹ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Akọ̀pẹ bẹ̀rẹ̀ ìṣẹ́sí iṣẹ́ ẹmu dídá; bẹ́ẹ̀ni Àwẹ̀’kún ṣíṣe apẹja tí ó sì lókìkí láàrín ìlú, nítorí ẹja rẹ̀ a máa tóbi.Ní ọjọ́ kan, ìjàpá lọ sí ààfin ọba láti sọ fún ọba wípé àwọn ọmọkùnrin yìí fẹ́ da ìlú rú..
wikipedia
yo
Ìjàpá dáhùn wípé àwọn ọmọkùnrin náà ń parọ́ káàkiri wípé àwọn lè ṣe ohun abàmì tí ẹ̀dá kan kò le è ṣe..
wikipedia
yo
Èyí tí ó ti ẹ yámi lẹ́nu jùlọ , òun ni eléyìí àbígbẹ̀yìn, ó ní òun le è wẹ́ okùn jà láàrín ìṣẹ́jú kan..
wikipedia
yo
Ha! Kábíyèsí , ohun tí ó fbámi lẹ́rù ni pé, àwọn ìlú tí ó yí wa ká, tí wọ́n bá gbọ́ ọ̀rọ̀ tí àwọn ọmọkùnrin yìí ń sọ nípa pé àwọn le è ṣe iṣẹ́ abàmì I yìí , ìlú wa yíò di ìlú àwọn rọ́rọ́ eléyìí nì sì leè mú àbùkù wá fún wa, Kábíyèsí..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n dé ààfin, ó pàṣẹ fún wọn pé lẹ́hìn ọjọ́ meje, ọ̀tárun gbọdọ̀ mú ọfà wá láti ta, kí ọfà náà kan òfúrufú..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọkùnrin yìí bẹ ọba , wọ́n ní àwọn kò mọ ìdí ọ̀rọ̀ tí ọba fi lọ àwọn yìí , àwọn ó sì mọ ìdí tí ọba fi ń bínú sí àwọn ..
wikipedia
yo
Ọba dáhùn pé a ti fi tó òun létí wípé àwọn ọmọkùnrin yìí ń fọ́n-nu pé àwọn le è ṣe ohun abàmì..
wikipedia
yo
Òun sì fẹ́ kí wọ́n ṣe gbogbo nǹkan tí wọ́n ń fọ́n nù pé àwọn lè ṣe..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn èyí, ọba pàṣẹ fún àwọn dògárì rẹ̀ pé kí wọ́n máa ṣọ́ àwọn ọmọ ìyá mẹtẹẹta náà, wọn kò sì gbọdọ̀ jẹ́kí wọ́n kúrò láàrin ìlú..
wikipedia
yo
Inú àwọn ọmọkùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta náà bàjẹ́ gbáà ; wọ́n mọ̀ pé ìjàpá ni ó wà nídìí ọ̀rọ̀ yìí , ṣùgbọ́n wọn kò mọ ohun tí wọ́n le è ṣe..
wikipedia
yo