cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ó jẹ oúnjẹ tí wọ́n ń fi ìrẹsì ṣe, tí wọ́n sì ń fi ọbẹ̀ miyar kúká, miyar kúBewa, àti miyar taushe jẹ́ ọ̀nà méjì ni wọ́n fi ń se oúnjẹ yìí, wọ́n lè fi àgbàdo ṣe(èyí tí wọ́n pè ní túwọn mására), wọ́n sì lè fi ìyẹ̀fun ọkà ṣe(èyí tí wọ́n ń pè ní túwọ́n dáwà)...
wikipedia
yo
OJI Rice tabi iresi ọ̀fadà jẹ ọkan lára awọn ounjẹ Yorùbá..
wikipedia
yo
O jẹ orukọ ti wọn fun iresi ti wọn gbin ni ilu ọ̀fadà ni agbegbe Obafemi Owode Ipinle Ogun..
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń gbin ní gúúsù apá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà ṣùgbọ́n orúkọ ìlú náà ni wọ́n fún..
wikipedia
yo
Wọ́n fi ìrẹsì ọ̀fadà ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn oúnjẹ yìí sì jẹ́ àṣepọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn nkan míràn tí wọ́n fi kún àwọn àṣepọ̀ yìí kĩ ṣe láti Nàìjíríà tàbí Áfríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n ń gbin ìrẹsì ọ̀fadà ní ilẹ̀ olómi.Àwọn ìtọ́kasíàwọn onjẹ..
wikipedia
yo
Abacha jẹ́ ọ̀kan lára àwọn oúnjẹ ẹ̀yà Igbos ní gúúsù apá ila oòrùn Nàíjíríà.Awon èròjà ounjé náà * ẹgẹ́ gbì u u tàbí UK̀pakà epo òpọ̀ tí Gberefu ẹja pọ̀ń gígé́dù gígé ijó ìkan ìkan tí wọ́n ti gé iyọ̀ àti atà ògbí gbí Maggi Nutbo ògiri ògiri aṣezi omi gbo gbó ní omi..
wikipedia
yo
Kunu (ti a tun mọ si Kunhanss ) je je okan lara awon ikan mimu ti o gbajumọ kakiri orile-ede Naijiria, pupo julọ ni Ariwa Naijiria..
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń sábà fi jéró tàbí ọkà ṣe, nígbà míràn, wọn ó lọ àgbàdo..
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń ṣe nípa rí rẹ̀ jéró tàbí ọkà tí ó ti gbó sí omi fún Ijó díẹ̀ tí wọn ó sì lọ̀ ọ́ mọ́ Odùkwu, atalẹ̀ tàbí ata...
wikipedia
yo
Banga Rice jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìrẹsì ní Nàìjíríà tí wọ́n fi ẹyìn àti ọbẹ̀ ẹ̀yìn ṣe..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà Urhobo ní apá gúúsù Nàíjíríà ni wọ́n ma ń sábà ṣe ẹ..
wikipedia
yo
Wọ́n ń pè ní ìrẹsì Banga nítorí bi wọ́n bá ti fún omi jáde lára ẹyin tán, wọ́n o fi se ìrẹsì..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà Urhobo kì í fi èròjà bí; Taìkọ́, Benetien, tàbí Rogòjé sí Banga Rice wọn bi wọ́n ṣe n fi sí ọbẹ̀ Banga wọn.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ẹran ìgbẹ́ túmọ̀ s'àwọn ẹran tí wọ́n pa ní inú igbó ó sì tún túmọ̀ sí àwọn ẹranko tí àwọn ènìyàn ń jẹ nínú igbó, pàá pàá jù lọ, ní ilé àdáwó..
wikipedia
yo
Ẹran ìgbẹ́ jẹ́ orísun àmù purotéènì ara fún àwọn ènìyàn Latin Amẹrika àti àsíá..
wikipedia
yo
O tun jẹ orisun ounjẹ fun awọn ẹlomiran, paa paa julọ awọn Talika ni igberiko..
wikipedia
yo
Jije ẹran ìgbẹ́ wa lara ohun ti o le sokunfa aisan ara bi Ebola virus ati HIV wa lati ara ẹran agba.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Emmanuel Nwankwo, tí a tún mọ sí Emmy gẹ́ẹ́, jẹ́ olórin ilẹ̀ Nàìjíríà tó ń gbé ní orílẹ̀-èdè South Africa..
wikipedia
yo
Orin àdàko akoko re "DOID and nairas" wa nipo keje láàárín awon orin ori atẹ ni ile South Africa..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gba orin sílẹ̀ nígbà tó wà ní ọmọdun mẹ́rìndínlógún, ó sí i síṣe pẹ̀lú Shidechai ń ọdún 2004..
wikipedia
yo
Ó jùmọ̀ ṣe ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ kan, tí wọ́n ń ṣe ohun ìdánílarayá àti aṣọ tí a mọ́ teamTalkless.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti orin àkọ́kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Emmy gẹ́ẹ́ sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, láti ẹ̀yà ìbò..
wikipedia
yo
Ó ṣe àṣeparí ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní Nàìjíríà kí ó tó kó lọ sí ilẹ̀ South Africa..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe ìgbéjáde orin àdákọ alákòókò Emmy gẹ́ẹ́ "Ránds and nairas" ní ọdún 2013.Àtòjọ orin rẹ̀orin àdákọgẹ́gẹ́ bíi àfifún olórinàwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹàwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèkàn singers, hip hop singers, male gbọ̀ns-21st-Century Nigerian Mamale singers1986 Births..
wikipedia
yo
Amarachi Uyanne ( Wọ́n bí ní 17 Oṣù Keje, 2004), ó gbajúgbajà gẹ́gẹ́ bi i Amarachi, ó jẹ́ ọmọdé-ọ̀dọ olórin Nàìjíríà, oníjó a sì tún mọ̀ ọ́ fún ìlò irinṣẹ́ violin rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló mọ̀ ọ́ gẹ́gẹ́ bí i olúborí ìdíje Nai·s's got Talent ti àwọn ọ̀dọ́.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Amarachi jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Delta..
wikipedia
yo
Wọ́n tọ́ dàgbà ní ìpínlẹ̀ Edo, ní ibi tí ó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní jó láti ọmọ ọdún 5..
wikipedia
yo
Ni 2012, o tayo gege bi i olubori idije akoko Nigeria's got Talent pelu ebun owo N10,000,000..
wikipedia
yo
Eyi fa a ki wọn ma pe e ni "oni Milionu kekere Nàìjíríà".Eko kíkó o lo ile-eko University Preparatory Secondary School ni ilu Benin, Ipinle Edo..
wikipedia
yo
Olókìkí ọmọ naa ṣẹ̀ṣẹ̀ kàwé gboyè ni ilé-ìwé náà ní oṣù keje, 2019..
wikipedia
yo
Ti o sese dara po mo ile-eko giga Benson Idahosa University, Benin, Ipinle Edo, Naijiria.Iṣẹ after emerging as the jáwọ́ of Nigeria's Got Talent, Amarachi released her debut single Mordekai "Amara Dance"
wikipedia
yo
Bi o di olubori idije Nigeria Got Talent, Amarachi ṣe agbejade orin akọkọ rẹ “Gchi Dance"
wikipedia
yo
ó tún tẹ̀síwájú láti fi olórin Phyno sínú orin rẹ̀ “ova Sabi”, orin rẹ ta gan-an bẹ́ẹ̀ ó gbà àwọn ìwúrí tó tẹ́rùn láti ọwọ́ àwọn lámèyítọ́ ajẹmó..
wikipedia
yo
lọ́wọ́lọ́wọ́ ó n dára Amarachi Talent Academy, ilé-ẹ̀kọ́ tí wọ́n tí n kọ́ àwọn ọmọ tí wọ́n ní ẹ̀bùn ijó àti orin bí wọ́n ṣe lè dàgbà sókè.Àgbájọ orin "Amarachi' Dance" "GE" Down" "AR Sabi BVIft Phyno) “ Hanori Quiero" Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Iresi Alapinnu joloofu (), jẹ iresi àṣepọ̀ lati iwọ-oorun Afirika..
wikipedia
yo
Oúnjẹ yìí jẹ́ àdàpọ̀ ìrẹsì, tòmátì, àlùbọ́sà, àwọn èròjà amóúnjẹ-ta-sánsán, ẹ̀fọ́ àti ẹran papọ̀ sínú ìkòkò kan, pẹ̀lú èròjà, àti pé oríṣiríṣi ọ̀nà ni àwọn èèyàn ń gbà ṣe oúnjẹ yìí níbikíbi.Ìtàn àti ìpìlẹ̀ṣẹ̀wọ̀n tó orírun ìrẹsì àsèpọ̀ jọloofu lósì agbègbè Sègábíàbíà lábẹ́ ìjọba jọ́loo tàbí wọ́loofu ní ọ̀rúndún kẹrìnlá, èyí tí Sèga, Gábíàbíà àti Moritẹ́nìa máa ń dín ìrẹsì..
wikipedia
yo
Orísun àti orírun oúnjẹ báyìí ni “Imkórìíraìkórìíra", ti ìrẹsì, ẹja àti ẹ̀fọ́ wà nínú rẹ̀..
wikipedia
yo
Òpìtàn ati ojogbon ounje ati ise ogbin James C..
wikipedia
yo
Ronú pé oun tí ó wà lókè bá tiẹ̀ jẹ́ òótọ́ nítorí bí ìrẹsì ṣe gbajúmọ̀ tó ní agbègbè Niger, àmọ́ ó tún lè jẹ́ pé òun gan ló fàá kìí ìrẹsì di ìlú mọ̀ọ́ká ni Sèga títí dé ibi tí ó dé.Ó wá dáabàá pé ìrẹsì náà tàn ká agbègbè Málì láàrín àwọn dyula àti èjìká tí ó di oun tí wọ́n fi ní ṣòwò, èyí tí wọ́n fi iṣẹ́ alágbẹ̀dẹ ṣe ìkejì, àwọn ìpolówó ọjà kékèké àti iṣẹ́ ìrẹsì.Marc Dufucasal, tí ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó gbọ́ gẹ́gẹ́ bí Émérìtus Professor ní ìmọ̀ ọ̀gbìn ọkọ̀ sọ pé ìrẹsì àṣepọ̀ jọ̀lọ̀ jọ̀lọ̀fu jẹ́ oúnjẹ ìgbàlódé, tí ó lè jẹ́ pé láti ipasẹ̀ àwọn Èèbó tí wọ́n ń dáko ẹ̀pà ni Sèga lábẹ́ ìjọba àwọn elédè Faransé tí wọ́n ń ṣe iṣẹ́ epo rọ̀bì, níbi tí ìrẹsì ó ti pọ̀, tí ó jẹ́ pé wọ́n lọ ń kó ìrẹsì àfọ́kù láti àsíá ní apá gúúsù ìwọ̀kk...
wikipedia
yo
It may then have JJad throughout the region through the Historical commercial, cultural and religious Channels linking Senegal with Ghana, Nigeria and beyond, many of which continue to thrive today, such as the Tijaniyyah Ṣufi brotherhood bringing thousands of West African Pilgrims to Senegal annually.Gographical range ati variantṣirésì jọ̀lọ̀fu jẹ́ oúnjẹ kan tí ó gbajúmọ̀ ní apá ìwọ̀ oòrùn ní Áfíríkà..
wikipedia
yo
Oríṣrí orúkọ àti èròjà ni wọ́n maa ń pè àti pé ni wọ́n maa fi ń see.; fún àpẹẹrẹ, ní Málì wọn a ma pè ní Zaame ní BANánkán..
wikipedia
yo
Jọ̀lọ̀fú jẹ́ orúkọ kan tí wọ́n yọ jáde lọ́dọ̀ àwọn ẹlẹ́dẹ̀ wọ́lọfu , àmọ́ ní Senegal àti Gábíàbíà, orúkọ tí àwọn èèyàn wòló ń pè túmọ̀ sí ceebu jën tàbí Benatẹlifíṣọ̀n..
wikipedia
yo
ní ọ̀dọ̀ àwọn elédè Faransé, Rizzo sì Grand ni wọ́n ń pè..
wikipedia
yo
Wàyí o, ladúrú gbogbo gbomísí-omi ọtọ yìí, bákan náà ni ó ti ṣe n rí ní gbogbo agbègbè yìí ti bó ti wá dìlù mọ̀ọ́ká ní Áfíríkà àti ní àgbáyé lápapọ̀.Àwọn èròjàìrẹsì jọ̀lọ̀fu jẹ́ àpapọ̀ ìrẹsì, òróró, ẹ̀fọ́ bíi tóátì, àlùbọ́sà,ata rodo, ata ilẹ̀, aáyù, ata ẹ̀bombo..
wikipedia
yo
Bákan náà ni wọn a máa fi àwọn èròjà dídùn bíi, iyọ̀, Magi, àwọn Spices mìíràn bí Curry, ati Taate láti tún bọ̀ jẹ́ kí ó tà sàn sàn..
wikipedia
yo
láti tún bọ̀ kìkì ó dùn rí, ẹran adiyẹ, tàbí vtókí, ẹja tàbí ẹran náà ó gbẹ́yìn tí ó máa ń bá ìrẹsì aláṣepọ̀ jọ̀lọ̀fu lọ.Regional variations and Rirry kí ní Afrika ni wọ́n ti ní oríṣi ẹ̀rọ, àti iyàtọ̀ àti bí wọ́n ti ń ṣe pàápa jùlọ láàrin àwọn ará Gánà, Nàìjíríà, sórí lórúkọlókè, Kamẹrúùn, Liberia, tí ó jẹ́ pé oníkálùkù ni ó pe orílẹ̀ èdè wọn ni ó ní jọ̀lọ̀fu tí ó dùn jù.. Aláṣẹpọ̀ jọ̀lọ̀fu jọ̀lọ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ọ̀nà ni wọ́n maa ń gbà irú ìrẹ̀sì (ìrẹsì ní Nàìjíríà, àmọ́ èyí tí ó jẹ́ ìpìlẹ̀ ni pé, tí a bá fẹ́ se ìrẹsì yìí, ìrẹsì tí ó gùn ni wọ́n maa sábà lọ, tó kékeré, ata rodo, òróró àti Magi..
wikipedia
yo
Gbogbo èròjà yìí, inú kókó kan ni gbogbo rẹ̀ yóo wà, èyí tí ọpọlọpọ ẹran, ata díndín ti wà nílẹ̀..
wikipedia
yo
nígbà tí gbogbo èròjà yìí bá gbóná tán ni a tó lè da ìrẹsì sínú ìkòkò náà, tí yóò sì fi wà lórí iná títí yóò fi jiná..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn gbogbo èyí ni, a lè bọ́ sí abọ́, tí a sì lè fi irú ohun mìíràn tí ó bá wun wa bí dòdò, Moi-Moi, ẹ̀fọ́, Saladìí àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Bí wọ́n ti ń ṣe ni; ní àkókò wọn máa bo ẹran pẹlu èròjà bíi, Magi, iyọ̀ àlùbọ́sà, aáyù, lẹ́yìn náà ni wọ́n máa rin ẹran náà, lẹ́yìn èyí ni gbogbo èròjà yòókù, náà máa wà ní díndín (àwọn ni, àlùbọ́sà, ata lílọ̀, tówhich lílọ̀, Magi ni tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn wọ̀nyí bá dín tán, a má da ìrẹsì sí inú ìkòkò ti ohun tí a dín wa, títí yóò fi jìnà tí wọn yóò fi bú sí abo..
wikipedia
yo
Wọ́n maa ń fi àwọn ohun bí ẹran díndín , adìyẹ tàbí tooki tàbí ẹja jẹ, àwọn mìíràn a ma fi ẹ̀fọ́ díẹ̀ sí orí ìrẹsì jọ̀lọ̀fu ti GÁNÀ.fún ayẹyẹ, wọ́n máa ń jẹ́ Gana jọ̀lọ̀fu pẹ̀lú Shito, èyí ti jẹ́ kiki dáa ata rodo tí ó wò ní orílẹ̀ èdè Gana, tàbí ṣaládìí ní àwọn ayẹyẹ mìíràn.Gbogbo mẹ́rìdù èdè BISè-guineàwọn máa ń fi àìga se ìrẹsì ṣe àdará yìí ní BISèyàn pẹ̀lú àwọn ohun bí TO bí líẹ̀; tí ó gbá, atá tún lírà tiré bí tí kò tẹ̀, tí kò yẹ, tí wọ́n pè ní M pé tí BAY..
wikipedia
yo
Gbogbo ohun tí a bíl yìí ni wọ́n máa dín nínú òróró gbóná pẹ̀lú èròjà tí ó ma ń jẹ́kí oúnjẹ tasánsán..
wikipedia
yo
Àwọn ará Bissau máa ń lo atalẹ̀ tí a mọ sì garlic láti le tún bo jẹ́kí oòrùn-ún tún bọ́ jáde sí..
wikipedia
yo
Ní ìgbẹ̀yìn, wọ́n ma ń jẹ ìrẹsì àṣepọ̀ yìí lásán tàbí pẹ̀lú ẹran adìyẹ, ilá tàbí dòdò.Ìtẹ́wọ́gbà rẹ̀ ní àgbáyéláti ọdún 2010 ní ìfẹ́ fún oríṣìíríṣìí oúnjẹ ti ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú ti ń gbòòrò lọ́kàn àwọn Èèbó aláwọ̀ funfun..
wikipedia
yo
Awon Eebo bere si ni se ajọdun fun iresi jọ̀lọ̀fu ti won se ni awon agbegbe bii Washington DC ni orile ede USA, Toronto ni Kanada ni won ti n se odun jọ̀lọ̀fu, eyi ti won se koja waye ni ojo laarin odun 2015 ti won pe ni World jollof Day, ti o si wun opolopo èèyàn lori ero ayelujara.Awon itọkasifun àkàsíwájú siWest Africa Stekópa Over jollof Rice War (BBC News, 2017) Rice dishesNigerian Cuibajadeeseese Cuìsìnhan Cuìsìneseneeseneleselese Cuìsìnnanan Cuetoetoetoleselese Cuisin African Cuẹ̀fọ́..
wikipedia
yo
BilKisu Kiyaran je oniroyin ni orile ede Naijiria oun si ni olori ẹka BBC lori iroyin ati nkan ti o n sele ni Afrika..
wikipedia
yo
ó kópa púpọ̀ nínú ìdá BBC Pidgin òun sì ni Oòotu àkọ́kọ́ fún BBC Pidgin..
wikipedia
yo
Ó wà lára àwọn alámójútó BBC Africa ẹyẹ Documentaries kí ó tó dára pọ̀ mọ́ BBC, ó jẹ́ olùkọ́ ní Yunifásítì Àmọ́dù Bello, Zaria, Nàìjíríà, òun sì ni adarí BBC World Service Trust ti ẹ̀ka Nàìjíríà.Ó gba àmì ẹ̀yẹ Master degree rẹ̀ ní Yunifásítì Àmọ́dù Bello Bello, Zaria, Nàìjíríà ó wà ní ipò karùn nínú àwọn obìnrin márùndínlo tí àjọ women in Journalism Africa kà pé ó lágbára jù ní ètò ìròyìn Nàìjíríà ní ọdún 2020.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Articles with Hcards), Joseph Adisa (tí a bí ní ọjọ́ keje Oṣù kọkànlá ọdún 1983) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria, agbẹjọro ati olóṣèlú ni, ó sì tún jẹ́ olókojọpọ, agbẹnusọ àti alabójútó ní ilé iṣẹ́ ìjọba..
wikipedia
yo
Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ Akọ̀wé agba fún Gómìnà nígbà kan rí ní Ìpínlẹ̀ Oyo, Sẹ́nétọ̀ Abiola Ajimobi ..
wikipedia
yo
Ní àkókò yí, ó jẹ́ ọmọ ilé Ìgbìmọ̀ asòfin ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà níbi tí ó ti ń sojú fún agbègbè Afijió lábẹ́ àgún ẹgbẹ́ All Progressive Congress (APC). Igbesi ayé àti Èkó á bí Seyi Adisa ní ìlú Èkó sínú ẹbí ẹbí àti Ìyáàfin Ebenezer Babátúndé Adisa ní ọjọ́ keje Oṣù kọkànlá, Ọdún 1983..
wikipedia
yo
Leo'S Nursery and Primary School, ilu Ikeja, ni Ipinle Eko..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ilé ẹ̀kọ́ alakọbẹrẹ, ó ré kọjá lọ sí ilé-ìwé girama tó gbajúgbajà ní ìlú Èkó, tí à n pè ní King's College, Lagos..
wikipedia
yo
Nígbàtí Seyi keko jade ni King's College, ó gba ilé ẹ̀kọ́ Lmbe College lọ láti gba ìwé ẹ̀rí tí a n pè ní a Levels lóri ìmọ̀ òfin, ìṣèlú àti okoowo, Àkọsílẹ̀ sọ wípé ó peregedé nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ nílé ìwé yìí..
wikipedia
yo
ṢÔṣèyí Adisa ko dara duro leyin eyi, o gba ile iwe giga Yunifasiti ti Birmingham (University of Birmingham) lo nibiti o ti gba imo ijinle lori imo ofin. tun fakọyọ ni ile iwe to wa fun awon Amofin ti a n pe ni the Bpp Law School nibi ti o ti tayo lori bi a se n fi imo ofin sise se, Legal Practice course (LP)..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó padà dé sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ṣèyí fi orúkọ sílẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ àwọn amórì ti orílẹ̀-èdè yìí, Nigerian Law School tí ó sì tún ṣe dáada níbẹ̀..
wikipedia
yo
ṣèyí Adisa kò jáfara ninu ìlàkàkà rẹ̀ lati di akọ́ṣẹ́mọsẹ́ tó dáńgájíá nínú iṣẹ́ tó yàn ìyò nígbà tí ó gbé'le keko gboyè ní àwùjọ àwọn akọ̀wé àti alabojuto ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Institute of Chartered secretary and Administrators course tí ó sì gba àmì ẹ̀yẹ fún akẹ́kọ tó tayọ jùlọ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ akọ̀wé fún ilé isẹ́ Nàìjíríà àti olókoting (Corporating secretaryship) ní ibamu pẹ̀lú iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òṣìṣẹ́ ìjọba..
wikipedia
yo
Láìpẹ́ yìí ni ṣèyí Adisa keko gba oye eleekeji ni ile eko giga Yunifasiti ti Birmingham (University of Birmingham).ise ati iriri awon Ọjọ́ìbí ni 1983awon eniyan alààyèṣèyí pelu enikan ni oludasile ile-ise ti a n pe ni T&A Legal..
wikipedia
yo
Ilé-iṣẹ́ yìí jẹ́ Àgbáríjọ àwọn agbẹjọ́rò, wón sì ṣetán láti ṣiṣẹ́ fún olúkúlùkù tí ó bá nílò iṣẹ́ wọn..
wikipedia
yo
Ilé-iṣẹ́ yìí bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú agbẹjọ́rò méjì péré ṣùgbọ́n láàrín ọdún mẹ́jọ, wọ́n di mẹ́ta-dín-lógún tí óósì wọn sì di mẹ́ta..
wikipedia
yo
Seyi ní ilé-iṣẹ́ yìí fi sí ìso wáká onibara, ó sì mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ onibara tí ó kún fún fún-iṣẹ́ ńláńlá láti òkè òkun, ilé-iṣẹ́ ìjọba pẹ̀lú àwọn aláólójì kòrírí láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà wá bá t&A Legal dá owó pọ̀..
wikipedia
yo
Ṣaaju asiko idasilẹ ile-iṣẹ t&a Legal yii, Seyi ti ba Ile-iṣẹ Agbẹjọro kan ti a n pe ni Adepetun Caxton-Martins Ami & Segun ṣiṣe ni ẹka epo epo ati isuna owo fun iṣẹ akanṣe.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Bob jẹ́ pé Òfin wa nípa tẹ́tẹ́, ọ̀pọ̀ àwọn ilé kàlòkàlò (kásino) tó wà ní Nàìjíríà kò ní ìwé-àṣẹ látọwọ́ ìjọba..
wikipedia
yo
The Federal Palace Hotel ni ilu Eko ni Kasino to tobi julo ni Naijiria wa..
wikipedia
yo
Agbòǹgbò ugh (tí wọ́n bí ní March 19, 1986) jẹ́ olùkọ̀wé àti olùṣe àti olùfi ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ eniyan mọ arese si Smart Money Aroko, orukọ ti wọn fun nitori fíFI rẹ; Smart Money Woman ati ilé-iṣẹ́ rẹ; Smart Money Africa.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹpẹ ati ẹkọ rẹ wọ́n bí Arẹse sí inú ìdílé Victor ati Funke Gemwọnyi ni Ilu Benin, Ipinle Edo, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O gba ami eye Bachelor's degree ninu imo iṣowo ninu ile iwe iṣowo aston, ati ami eye master degree ninu imo Economics Development ni ile iwe College Yunifasiti ti London..
wikipedia
yo
O tun kawe ni ile iwe iṣowo ipinlẹ Eko(Lagos Business School) ati London Business School.Iṣẹ rẹ ninu akitiyan rẹ lati ran awọn ọmọbinrin lọwọ ninu eto isuna wọn, Aiku ughwu da Smart Money Africa silẹ..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ náà jẹ́ ẹgbẹ́ tí ó ran àwọn ọmọ lọ́wọ́ lati kọ́ nípa ètò ìunàn ní ọnà tí ó rọrùn..
wikipedia
yo
Ète areṣe ni láti yí ìtàn àìní ní Afrika pada nípa kiko awon eniyan nipa eto isuna..
wikipedia
yo
Agbòǹgbòṣe ma ń lo oríṣiríṣi ìtàn láti fi kọ́ àwọn ọmọ Áfríkà nípa ètò ìṣúná,ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà sì ni ó ma ń lo àwọn oríṣi ìtàkùn ayélujára..
wikipedia
yo
Abaaṣẹ tun ni oludasile Smart Money Travel ní ọdún 2016, ó kọ ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́ tí àrí rẹ̀ jẹ́ 'The Smart Money Woman - an African Girl Journey to Financial Freedom
wikipedia
yo
Ní ọdún 2020 ṣe fípapọ̀ kan lórí ìwé rẹ̀.Ause ma n ṣe ètò kan tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ "Your Life, Your Money" lórí Guardian's TV.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Sodiq Abubakar Yusuf (ibi jẹ́ May 6, 1985), ẹni tí àyè mọ̀ sí CDq, jẹ́ olórin, ọ̀kọrin tí ó jẹ́ gbajú gbajà jẹ́ ọmọ bíbí ikẹ̀ Nàìjíríà tí ó kọ “Okúnkún sókè tí olórin Wizkid náà kópa nínú orin náà àti Ọládé tí í wà lábẹ́ Master),[4..
wikipedia
yo
nígbà kan rí ó máa ń lo ohun èlò orin kí ó tó sùn sí orin ti jẹ́ kí ó gba àmì ẹ̀yẹ ní ọdún 2016 ní Nigerian Music Video Awards..
wikipedia
yo
Labẹ ile ise orin No struggle, No Success Entertainment, Oso fun CDq ti fi orin Rap si abẹ́ ẹya iru orin ti CDq n kọ, awon bii woss wòbí ti o kọkọ bẹrẹ.ibẹrẹ Aye ati eto Eko Sodiq Abubakar Yusuf jẹ ọmọ ilu Ilorin ni Ipinle Kwara, ni orile edè Naijiria; amo won bi si orile ti o wa ni Ipinle Eko..
wikipedia
yo
Leyin ti o wa si Eko lati Ilorin ni o pari eko sekondiri re, o tesiwaju ninu eko re ni ile iwe Fasiti ti wa ni ilu Eko, Lagos State University nibi ti o ti gboye B.Sc ni ìkọ́omiKiṣi (Economics)ọ̀kọrin CDq yáa opolopo eeyan lenu nipa fifun awujo pada ati ki a maa se iranlọwọ ni awujo..
wikipedia
yo
Ní ìpínlẹ̀ Kwara ni ó ti ṣe èyí.Bákan náà, ọ̀kọrin CDq lọ sí ààfin ọba ìlú Ìlọrin nígbà tí ó kọ́kọ́ wọ inú ìlú náà láti lè fi tó ọba létí nípa èrò rẹ̀ fún àwọn ọmọ sẹ́kọ́ndírì tí ó wà nínú ìlú náà.Lílò tí ó lọ, ọjọ́ méjì ni ó fi dúró sínú ìlú náà, láàrín ọjọ́ méjì yìí náà ni olùdarí ilé ìwé náà ti ṣe ìgbàlejò CDq àti àwọn ẹmẹ̀wà ẹ̀, tí olùdarí ilé ẹ̀kọ́ náà sì pe àwọn ilé ẹ̀kọ́ náà sí tà, èyí tí àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ náà gba ẹ̀bùn..
wikipedia
yo
9olórin CDq fún àwọn ọmọ náà ní ohun ìkọ̀wé àti aago.
wikipedia
yo
Ìgbà yìí ni agbẹnusọ olórin náà pé “ iṣẹ́ àgbéṣe yìí wá láti ri pé àwọn ọmọ ilé ìwé wọn kò ní ìṣòro lórí ohun tí a fi ń kọ̀wé, tí ipinlẹ náà yóò gba àwọn ànfààní tí ó sodo sínú ohun tí wọ́n fẹ́ ṣe.Iṣẹ́q bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin ní ọdún 2008 nígbà náà ni ó jẹ́ ẹlẹgbẹ́ ọ̀kọrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ bíGrin kí ó tó bẹ̀rẹ̀ orin Rap ní èdè Gẹ̀ẹ́sì pẹ̀lú M.I Abaga..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2013 , ó dara pọ̀ mọ́ MasterBER (producerproducer) tí wọ́n sì fi òǹtẹ̀ lu ìwé lẹ́yìn ìgbà tí ó gbé ipò kíní nínu ìdíje Industry Nite ní Oṣù Kọkànlá Ọdún 2012..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ó kọ orin tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Indomie ti Olamide àti Davido naa wà ninu orin naa, ti o si kàn jale orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Orin ti CDW kọ lábẹ MasterBERft ló gbà jáde tí ó fi di olókìkí àti pé ó jẹ́ kí wọ́n yàn-án fún gbígba àmì ẹ̀yẹ Nigeria Entertainment Awards ní 2015 àti Best Street hop artist ni Headies.Ni ìfojúsọ́nà fún album rẹ̀ tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní Qukáìty CDq tí olórin Wizkid náàa wà nínú rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ n'ọwọ́ ẹ̀ sókè jẹ́ orin tí ó jẹ́ kí album àwo orin náà Tam kalẹ̀..
wikipedia
yo
Oludari fidio Orin naa ni Unlimited l.A, ti o si gba ami ẹyẹ Best Afro hip hop Video ni ọdun 2016 ni Nigeria Music Video Awards..
wikipedia
yo
ON 16 August 2016, he unveiled the COVER art for the album before it was released through general Records on 22 August to positive Critical Reviews..
wikipedia
yo
On 11 November 2016, he launched his own record label n.S.n.S, a short-form for no struggle no success entertainment..
wikipedia
yo
On 1 Feb 2017, he Oludara His First Official Single Under the Platform Ijọbals ‘ Say ' which was produced by Jay Pizzle.Awo Orinmíràn Singles Albums*_pàṣẹ23 Mugabe Aaami Eyeawọn itọkasi1985 Birth Eniyan AAlààyèpeople From ÌlọrinNigerian DosLagos State University Alumníní SongWriters Songst hop hopary..
wikipedia
yo
Micheal Taiwo Akinkún OFR ti won bi ni ojo ojo, osu karun-un odun 1936,je gbajugbaja osise se feyinti omo orile-ede Naijiria to disaini Fulagi apapo orile-ede Naijiria.inagijẹ re ni Ogbeni Fulagi.Ìgbésí ayé àti ise reametakun je omo bibi ilu Ibadan,ẹ̀yà Yoruba, Omotayẹ̀wò agba ibeji..
wikipedia
yo