cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Irú àwọn ewì bẹ́ẹ̀ ni ó ti wà ní kíkọ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èdè, pẹ̀lú Arabic, Kurdish àti Turkish..
wikipedia
yo
Àwọn bí ayẹyẹ Mawlid 3,000 ni wọ́n má ún ṣe ní ìọdọọdún..
wikipedia
yo
Àwọn eniyan káàkiri àgbáyé ni wọ́n má ún ṣe àwọn àjọ̀dún náà..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ, àwọn ènìyàn tó tó mílíọ̀nù mẹ́ta ni wọ́n ma ún kópa ní Ahmad Al-Badawí, ènìyàn mímọ́ Súfì ní 1200 àwòránàwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Kadiri ikHana (ti won bi lọjọ kokanlelogbon osu kejila odun 1951) je agbaboolu-afẹsẹgba fun iko egbe agbaboolu,Kano Pillars nigba kan ri, ti o wa di akonimọ boolu-afẹsẹgba omo Nigeria.Iṣẹ agbabooluikHana gba boolu-afẹsẹgba jẹun pelu iko Bendel Insurance, ti won sin gba ife-eye liigi agbata lodun 1978 ati 1980.Hana wa lara iko egbe agbaboolu Nigeria ti won ṣoju orile-ede naa lati gba idije-osere fun idije Ife agbaye FIFA ti won gba dije ninu idije Olympics lodun 1980..
wikipedia
yo
O wa lara iko egbe agbaboolu Nigeria ti won gbe igba orókè ninu idije, 1980 African Cup of Nations.Iṣẹ re gege bi akọnimọgabaHana ti sise akọnimọ fun orisirisi iko egbe agbabọọlu ke, lara won ni; el-kanemi warriors f.C., BCc Lions f.C., Kwara United F.C., Sunshine Stars f.C., Sharks f.C..
wikipedia
yo
Ati Gíwá F.C..AHHana ni akọnimọ ìkó ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù enyímba International F.C..
wikipedia
yo
Lórílẹ̀-èdè tí wọ́n gba ifẹ́-ẹ̀yẹ, African Champions League lọ́dún 2003..
wikipedia
yo
Ọdún yìí náà ni wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí akọnimọọgba tí ó dára jù lọ..
wikipedia
yo
In 2004, he was manager of the Nigerian men's Olympic team.Lẹ́yìn náà ó ṣiṣẹ́ akọnimọọgba fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Kano Pillars f.C., kí ó tó kọ̀wésílẹ̀ lóṣù kaàrún ọdún 2008, pẹ̀lú ìbòsí ìwà àjẹbánu nínú àjọ eré-ìdárayá tí ó ké fún ìdí tí ó fi ṣe bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
He had led Kano Pillars to their first ever League title a day earlier.Wọn yan an ní akọnimọ àwọn iko egbe agbabọọlu-obinrin ti orile-ede Nigeria lóṣù kẹrin ọdún 2012, kí ó tó koweça lóṣù November, ọdún 2012.O ń sise akonimọọgba fun iko egbe agbabọọlu Nasarawa United f.C..
wikipedia
yo
Titi di osu November 2013 nigba ti o pinnu lati síwọ́ ise ere-idaraya..
wikipedia
yo
O tun pada si iko egbe agbaboolu enyimba, ti o sin tun gba ife-eye liigi agbabuta ki o to tun dara po mo àpótíting Stars s.C..
wikipedia
yo
O tun pada si iko Kano Pillars Eko November odun 2016, Before Being sacked in April 2017.Awon aṣeyọriaṣeyọri gege bi agbaboolupelu Bendel Dirancpípadà Premier League - 1979 FA Cup - 1978, 1980pelu niáa of Nations -aṣeyọri 1980 gege bi akoniNew yàráMọ́ Premier League League – 2015 Champions League – 2003 PilvNigerian Premier League League League ti o dara ti o dara ju lo lodun awon itọkasi
wikipedia
yo
jẹ iko egbe agba-Agbasise ni ipinle Kano ni Nigeria..
wikipedia
yo
Wọ́n maa ń kópa nínú ìdíje kékeré nínú ìdíje liigi agbabuta bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ti Nigeria..
wikipedia
yo
Wọ́n dá ẹgbẹ́ Kano Pillars yìí sílẹ̀ lọ́dún 1990, Ọdún tí bọ́ọ̀lù Agbasise bẹ̀rẹ̀ ní Nigeria, ẹgbẹ́ yìí jẹ́ àdàpọ̀ àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù abẹ́lé mẹ́ta ní Ìpínlẹ̀ Kano.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Bassey Albert Akpan(ti a bi ni ọjọ kejidinlogun Oṣu Kẹwa ọdun 1972) jẹ oloselu ni orile-ede Naijiria, ati Senato ile Igbimọ Asofin Naijiria lati June 2015..
wikipedia
yo
Kí ó tó dé ipò náà, ó jẹ́ ComiSion fún ètò owó ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom láti 2007 sí ọdún 2014.A kọ́kọ́ yan sí ipò Senato ní Oṣù kẹta ọdún 2015, láti ṣe aṣojú agbègbè Akwa Ibom, a si tún ti yan sí ipò náà ní oṣù kejì ọdún 2019..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ ẹgbẹ oṣelu People Democratic Party Naijiria.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
ọ̀dọ̀co Listira ti Sicilies meji xico ìpalára (Francis) (Naples, 19 August 1777 – Naples, 8 Kọkànlá Oṣu 1830)Ó jẹ ọba ti awọn Sicilies meji, ti o ni ilọsiwaju nla ni ijoba rẹ, awọn ọmọ rẹ wa ni ọpọlọpọ awọn ile ọba...
wikipedia
yo
Mallam Adamu Adamu Con (tí a bí ní 25 May 1954) jẹ́ ọ̀mọ̀wé oníṣirò àti oníròyìn ní Nàìjíríà, òun ni Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ ní Nàìjíríà .Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹa bí Ádámù ní ọjọ́ karùndílọ́gbọ̀n oṣù karùn(25 May) ọdún 1954, in Azare..
wikipedia
yo
Ó gba àmì ẹ̀yẹ nínú ìmọ̀ ìṣirò ní Yunifásítì ti Ahmadu Bello, Zaria..
wikipedia
yo
O tun pada gba ami eye Master's degree ninu imo iroyin ni School of Journalism ti Yunifásítì Columbia o le sọ Ede pupo, Ede bi Hausa, ingLisi, Persian, Arabic ati French..
wikipedia
yo
Ronald Chagoury (Ọjọ́ Ìbí Jesu Ọjọ́ Kẹjọ, Oṣù Kínní Ọdún 1949) jẹ́ oníṣòwò kan ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, òun àti àbúrò rẹ̀ Gilbert Chagoury ni wọ́n jọ dá ilé iṣẹ́ Chagoury Groupb sílẹ̀, wọ́n sì jọ jẹ́ olùdarí àti olùdásílẹ̀.Ìgbé ayéwọn bí Ronald Chagoury sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní ọjọ́ kẹjọ Oṣù Kínní Ọdún 1949, tí ó jẹ́ ọmọ RMez àti Alice Chagoury, tí wọ́n dì jọ kúrò ní Lẹ́bánọ́n ní ọdún 1949..
wikipedia
yo
Ó kàwé ní College des freres chrétiennetiens ní Lẹ́bánon, bákan náà ni ó kàwé gboyè nínú ẹkọ́ ìṣirò ní Fasiti tí ó wà California ní long beach ní orílẹ̀ èdè Amerika.1] ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Berthe, wọ́n sì sí jọ bímọ méjì. Chagoury tí jáde nínú ìwé ìròyìn ìròyìn PANAMA.Àwọn ìtọ́kasís-1949 èyítí Business Business-21st Nigerian BusinessPeople From From Lagos B BusinessPeopleCalifornia State University, Long Beach ríran àwọn ènìyàn Alààyè People of Lẹ́nilé E Descent Estate EstatePeople Gber In the Panama in the olúwas..
wikipedia
yo
Ronald Chagoury (tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù kìíní ọdún 1949) jẹ́ oníṣòwò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Chagoury Group pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n rẹ̀, Gilbert Chagoury.ìgbésíayé rẹ̀ wọ́n bí Ronald Chagoury sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù kìíní, ọdún 1949..
wikipedia
yo
Ó sì jẹ́ ọmọ Ramez àti Alice Chagoury tí ó kúrò ní ìlú Lẹ́baọ́n ní ọdún 1940..
wikipedia
yo
Ó kàwé ní College des freres chrétiennetiens ní ìlú Lẹ́bánon, ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ nípa owó ní California State University, tí ó wà ní long beach, ní US.chagoury fẹ́ Berthe, wọ́n bí ní ọmọ méjì papocha.ọlà ti yọ nínú ìwé Panama.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Nàìjíríà gba olómìnira ní àyájọ́ ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá 1960, ó sì di orílẹ̀-èdè Olómìnira ní ọdún 1963..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè yí ṣe àgbékalẹ̀ àmì-ẹ̀yẹ ìdánikan méjì kan kalẹ̀ láti ma fi bu ọlá fún àwọn lààmì-laaka ènìyàn láwùjọ..
wikipedia
yo
Orisorí àkọ́kọ́ yi jẹ́ àmì-ẹ̀yẹ tí ó tọ́ sí ẹnikẹ́ni tí ó bá ti jẹ́ Ààrẹ àti igbákejì Ààrẹ, olórí ilé Ìgbìmọ̀ asòfin, Adájọ́ àgbà fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìsọ̀rí àmì-ẹ̀yẹ náà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kọ́ṣẹ́ ìjọba ìjọba amúnisìn ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì nípa fífi àmì-ẹ̀yẹ dá àwọn lààmì-laaka àti ìgbòsí ìlú lọ́la..
wikipedia
yo
Àmì-ẹ̀yẹ yí ni ó wà fún àwọn ológun àti àwọn tí kìí ṣe ológun..
wikipedia
yo
Wọ́n sì ma ń kọ̀wé ránṣẹ́ sí àwọn tí wọ́n bá yàn láti fi àmì-ẹ̀yẹ náà dá lọ́lá..
wikipedia
yo
Ibrahim Muhammad tanko (ti a bi ni ojo kokanlelogbon, osu kejila, odun 1953) je adajo orile-ede Naijiriati o sin ni ile-ẹjọ ti o ga ju lo lati odun 2006 wo odun 2022, ati bii adajo agba ile Naijiria lati odun 2019 titi o fi ori ifi ifilẹ ranse ni osu kefa odun 2022 nitori ailera rẹ..
wikipedia
yo
ó fìgbà kan jẹ́ adájọ́ ní ilé-ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ tànkó jẹ́ ọmọ Fulani tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n, oṣù Kejìlá, ọdún 1953 ní Dogu-gi-adé tó jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ kan ní ìpínlẹ̀ Bauchi, tó wà ní apá àríwá ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ìwé girama ti ìjọba ní ìlú Azare, níbi tí ó ti gboyè wáEC ní ọdún 1973 kí ó tó lọ sí Fásitì Ahmadu Bello níbi tí ó ti gboyè ll.B..
wikipedia
yo
Ninu ẹ̀kọ́ òfin ní Faṣiti kan náà ní ọdún 1985 àti 1998 bákan náà.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Orin àpàlàbí irun ṣe súnmọ́ orí ni orin sí àwùjọ Yorùbá, pékí-pékí ni wọ́n súnmọ́ ara wọn..
wikipedia
yo
Yorùbá fẹ́ràn orin púpọ̀ tó fi jásí pé kò si igbà, àkọ́kọ́ tàbi ìṣẹ̀lẹ̀ kan ti Yorùbá kò lè ti kọrin àyààfi ìgbà tí wọ́n bá ń sùn tàbí tí wọ́n bá ń jẹun..
wikipedia
yo
Bí Yorùbá ṣe fẹ́ràn orin tó yìí, a rí pé orin wọn kò dúró sí ojú kan, bí ìdàgbàsókè ṣe ń bá àwùjọ wọn náà ni ìyípadà ń dé bá orin Yorùbá..
wikipedia
yo
Ní ìgbà kan rí, àwọn orin bíi rárá, ọ̀lẹ̀lẹ̀, obitun àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ní Yorùbá ń lò fún ìdárayá kí ọpọ́n tó sùn kan orin àpàlà tí a ṣiṣẹ́ lórí ẹ̀ yìí, ìgbà tí ó ya ní ayé tún sun kan Jùjú..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí ni Fújì kí ó tó wa kan táunsúfèé ti ayé ń jó lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí..
wikipedia
yo
Gbogbo èyí fi hàn pé orin Yorùbá kò dúró sí ojú kan..
wikipedia
yo
Lóòótọ́ a kò leè fi gbogbo ẹnu sọ ó pé àwọn orin tí a dárúkọ wọ̀nyí ti di ohun ìgbàgbé ṣùgbọ́n ayé kò gbọ́ wọn bí i ti tẹ́lẹ̀ mọ́, kí ọ̀rọ̀ àwọn orin yìí má baà di àfìsẹ̀yìn ti eégún fiṣọ ni mo fi yàn láti sọ̀rọ̀ lórí orin àpàlà.Orin àpàlà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn orin Yorùbá tí wọ́n jẹ́ gbajúmọ̀ ní agbègbè Ẹ̀gbá, Ìjẹ̀bú, Ọ̀yọ́, Ọ̀ṣun àti Ìgbómìnà..
wikipedia
yo
Orin ìgbafẹ́ ní orin àpàlà....olóògbé Haruna ìṣọ̀lá ni a gbà pé ó dá orin àpàlà sílẹ̀, àjogúnbá sì ni iṣẹ́ orin jẹ́ fún-un nítorí pé àwọn bàbá bàbá rẹ̀ ti ń kọrin tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Olórin ni Bello tii ṣe bàbá Haruna Ishola gan an bẹ́ẹ̀ olórin ni egúngúnjobí tii se bàbá Bello náà ṣùgbọ́n orin tí wọ́n ń kọ nígbà náà kìí ṣe àpàlà, Sengbè ni orúkọ tí wọ́n pe orin tiwọn nígbà náà, àwọn kìí sì lu ìlù sí orin tiwọn, àdàkọ orin lásán ni, kí olóògbé Haruna Ishola tó bẹ̀rẹ̀ sí ní lu ìlù sí orin tirẹ̀ Èyí tí o di orin àpàlà yìí..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìyapa ẹnu pọ̀ lórí èyí, síbẹ̀ ipa olóògbé hárúnà ìṣọ̀lá lórí bí orin àpàlà ṣe bẹ̀rẹ̀ kó mọ níwọ̀n..
wikipedia
yo
Àwọn mìíràn tó tún kọrin àpàlà ni olóògbé àyìnlá Ọmọlí, adégétọ̀, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé lórí orin àpàlà, péÀàrẹ òkìkí0820204112/08122727..
wikipedia
yo
Olajide Olayinka Williams " JJ " Olatunji (Ọjọ́ìbí 19 Oṣù Kẹfà 1993), tí a mọ̀ sí akosemose KSI, ó jẹ́ olórin tí Gẹ̀ẹ́sì lórí YouTuber àti afẹṣẹja ..
wikipedia
yo
O jẹ oludasile ati ọmọ ẹgbẹ ti ẹgbẹ YouTube ti Ilu Gẹẹsi ti a mọ si Sidemen ..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ Alákoso ti Misfits Boxing àti alọ́jọ́ni Prime Energy drink , XIX Vodka àti ilé oúnjẹ kan tí a mọ sí àwọn ẹgbẹ.KSI forukọsilẹ lórí YouTube rẹ ni ọdun 2009 o si kó àwọn fidio àsọyé àsọyé ifiweranṣẹ atẹle ti jara ere fidio FIFA ..
wikipedia
yo
ÀkóÀkó YouTube rẹ̀ padà di vlog àti àwọn fidio aláwàdà..
wikipedia
yo
Ni Oṣu Kẹwa ọdun 2022, o ni awọn alábàápín ti o ju 41 milionu ati bi awọn iwo fidio bilionu mẹwa ti o kọja awọn ikanni YouTube rẹ mẹta.Awọn eniyan Alààyèawọn Ọjọ́ìbí ni 1993articles with Hcardṣàwọn àyọkà pelu Ìjúwe soki..
wikipedia
yo
Ilé-ẹjọ́ ní ibi tí ìjọba gbé kalẹ̀ tí wọ́n sì fi àṣẹ sí wípé kí ìgbẹ́jọ́ àti ìdájọ́ èyíkéyí tí ó bá láìe hù láàrín àwùjọ ó ti má wáyé pẹ̀lú ìlànà òfin ìjọba orílẹ̀-èdè náà..
wikipedia
yo
Àti ìbú àti ọ̀rọ̀ ètò ìdájọ́ orílẹ̀-èdè kan, ilé-ẹjọ́ ní ibi tí adájọ́ ti ma ń fi ẹsẹ̀ òfin ṣe ìgbẹ́jọ́, ìdájọ́ àti ìpẹ̀tù-s'aáwọ̀ láàrín àwọn ènìyàn, ìlú tàbí ilé-iṣẹ́ méjì ti ìjà , tàbí ajì-jà bá ti ń wáyé nígbà tí wọ́n bá gbé ẹjọ́ wọn wá sílé ẹjọ́..
wikipedia
yo
Ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá f'ẹ̀sùn kàn nílé ẹjọ́ ní àǹfàní láti gba agbẹjọ́rò tí yóò jẹ́ agbẹnusọ fún níwájú adájọ́àṣẹ ìgbẹ́jọ́àṣẹ ìgbẹ́jọ́ ni a lè pè ní àṣẹ àti agbára ti ilé-ẹjọ́ tàbí adájọ́ ní láti gbé ìdájọ́ kalẹ̀ ní ọ̀nà tí ó bá òfin mu nínú ìlú àti orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà.Ǹjẹ́ ilé-ẹjọ́ tàbí adájọ́ ní ẹ̀tọ́ láti gbọ́ ẹjọ́ tí wọ́n bá gbé wá sí iwájú wọn jẹ́ ìbéèrè kan pàtàkì tí ó yà kí ènìyàn ó bèrè..
wikipedia
yo
Oríṣi ìdájọ́ mẹ́ta ló wà, àkókò ni ìdájọ́ lórí ènìyàn, èyí ni ìdájọ́ lórí ohun tí ó jọ mọ́ ènìyàn àti ohun ìní wọn..
wikipedia
yo
Ikeji ní ìdájọ́ lórí ìṣẹ̀lẹ̀, èyí ni kí wọn gbé ìdájọ́ kalẹ̀ l'orí ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ láwùjọ, ìkẹta ni ìdájọ́ ilẹ̀tí ààlà-ilẹ̀..
wikipedia
yo
àwọn ìdájọ́ mìíràn tí ó tún wà ní ìdájọ́ gbogbo-gbọ́, ìdájọ́ adágbọ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Kòkòrò jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ àwọn Yorùbá àwọn nǹkan tí wọ́n f ṣe é ní àgbàdo, ṣúgà, èlùbọ́ tàbí Gari gbígbẹ.O ṣe é tọ́jú fúngbà pípẹ́ tí a bá gbé e pa mọ́ kúrò níbi tí atẹ́gùn wà..
wikipedia
yo
Oríṣi kòkòrò méjì ni ó wà, àwọn ni kòkòrò gbẹrẹfu àti aláta.Lẹ́yìn tí a bá ti da àgbàdo gbẹrẹfu sínú omi gbígbóná, a máa ro ó pọ̀ dáadáa..
wikipedia
yo
Abula jẹ́ ọ̀kan lára ọbẹ̀ àwọn Yorùbá ní ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà..
wikipedia
yo
wọn ma ń sábà jẹ ọbẹ̀ naa pẹ̀lú àmàlà, ṣùgbọ́n o ṣe fi jẹ àwọn oúnjẹ òkèlè mìíràn..
wikipedia
yo
Àdàlù oríṣi ọbẹ̀ ni Abula túmọ̀ sí, ṣùgbọ́n ṣùgbọ́n ó ma ún sábà túmọ̀ sí àdàlù gbegiri (ọbẹ̀ ẹ̀wà), Ewedu àti ọbẹ̀ ata..
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń ka Abula sí ọbẹ̀ aládùn kò sí un ṣe ọbẹ̀ tí wọ́n dédé ṣe..
wikipedia
yo
Àwọn Yorùbá ní ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà ni o ma ún sábà se ọbẹ̀ yìí, pàá pàá jùlọ, àwọn èèyàn Ọ̀yọ́ àti Ògbómọ̀sọ́.Wo èyí náà ̀wón àwọn ọ̀bẹ ní Nàìiregìrì ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Okpa jẹ ounjẹ ilẹ̀ ibo ti wọn maa n fi epa Bambara ṣe..
wikipedia
yo
O wọpọ laarin àwọn eniyan to wa lati Ipinle Enugu, wọn si ka a mọ ounjẹ ibilẹ Naijiria..
wikipedia
yo
Kìí ṣe àwọn ìbò nìkan ló ń jẹ́ ọkpa, àwọn ẹ̀yà mìíràn máa ń jẹ́ ọkpa pẹ̀lú ògì tàbí kí wọn jẹ ẹ́ lásán..
wikipedia
yo
Orúkọ mìíràn tí wọ́n máa ń pe Okpa ni; igba ati ńtúcha..
wikipedia
yo
Àwọn Hausa máa ń pe ẹ ní Gurjìyà tàbí Kwarúrú.Àwọn aworaǹàwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Moi-Moi tàbí Kera-mọ́in jẹ́ ẹ̀wà lílọ̀ sísè tí ó jẹ́ pé àwọn èròjà rẹ̀ ní ẹ̀wà bíbọ̀, tí wọ́n ṣáábà ṣe pẹ̀lú àlùbọ́sà, táfọ́n (rodo,ata gígún), òróró, edé abbl.A tún mọ Moi-Moi sí “Ale” tàbí “ọ̀lẹ̀lẹ̀” ní àwọn ẹ̀ka-èdè Yorùbá mìíràn, bẹ́ẹ̀ bí àwọn ènìyàn ṣe mọ̀ ó sí ní Sierra Leone àti Gánà..
wikipedia
yo
Tukọjá (tàbí Dáhun) jẹ irúfẹ́ oúnjẹ yìí( Moi-Moi) ní apá àríwá ilẹ̀ Gánà..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń fi gàárì, kòkó, tàbí kósítadì jẹ́ Moi-Moi náà..
wikipedia
yo
O tun jẹ ounjẹ-afikeẹgbẹ ni awọn inawo Naijiria, ti wọn n fi kun iresi alẹsepo ati irúfẹ awọn ounjẹ mìíràn.Àwọn ohun-elo ẹ̀wà, tatase, ata rodo, òróró, tòmátì (fún pípọ́n èyí kì í ṣe dandan), ede lilọ (bi o ba ṣe tẹ ọ lọrùn), àlùbọ́sà to bá to, ẹyin tabi awọn ẹran wẹ́wẹ́, tabi irúfẹ́ ẹran to ba wù yín, tabi ẹja yíyan, tabi ẹja aláìlègun bíbọ̀, ìsebẹ̀/iyọ ati Magi, omi naa ni ìwọnba.Ìlànà ṣíṣe ní akọkọ ni lati rẹ ẹwa sinu omi tútù, kí epo ara rẹ le rọrùn lati ṣi kuro patapata titi to ma fi funfun..
wikipedia
yo
kí o sì lọ tí kò fi ní ẹwà líle kankan mọ pẹ̀lú ẹ̀rọ-ìlò..Ta
wikipedia
yo
Nínú abọ́ fífẹ̀ ti ẹwà lílò náà wà á ṣe àfikún iyọ̀, Magi, èdè gbígbẹ, òróró, àti àwọn ohun-èlò ìdáná mìíràn láti fún ládùn..
wikipedia
yo
Àwọn mìíràn máa ń fi oríṣi ẹja tàbí ẹyin, tàbí ẹran wẹ́wẹ́ sínú rẹ̀ náà..
wikipedia
yo
èròjà rẹ̀ tó máa ń pọ̀ yìí, máa ń mú kí tí ó sì máa ń mú kún inú èèyàn ní ìjẹ ìtẹ́lọ́rùn..
wikipedia
yo
Èyí ló tún fà á tí àwọn ènìyàn ṣe máa ń pè é ní Kera-mọ́in èléẹ̀mí méje.Kin-mọ́in usually comes in a ṣlanted pyramid shape, Cylinṣáájú shape, cone shape and any targéted shape oríṣiríṣi ìrísí tó bá wuni ni èèyàn lè gé Moi-Moi sí, pẹ̀lú ohun-èlò tó tó tó ìrísí tó wọ́pọ̀ jù ni èyí tí a máa ń fi ewé ẹran tàbí ewé ọ̀gẹ̀dẹ̀ yọ tí wọ́n máa ń fi ewé náà sínú ihò tí wọ́n ṣú pẹ̀lú àtẹ̀lé owó, tí wọ́n má wá bu ẹ̀wà lílọ̀ tí wọ́n ti fi èròjà pọ̀ pọ̀ sí, wọ́n sì má pọ́n..
wikipedia
yo
Àwọn ìsírí Mísí láti Ara pipọ́n sínú àwọn agolo Olorisí ìsísí ni wọ́n tí máa ń yọ wọ́n..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn pípọ́n sínú àwọn ewé tàbí àwọn agolo wọ̀nyí, wọ́n ma tò wọ́n sí inú abọ́-ìdáná pẹ̀lú omi ìdá ìlàjì àbọ̀-ìdáná náà, láti sẹ́ Moi-Moi náà jiná pẹ̀lú orù omi náà..
wikipedia
yo
Wọn maa n jẹ Moi-Moi lasan tabi pẹlu Burẹdi, pẹlu ìrẹsì tabi ògì fun ounjẹ àárọ̀ tabi ounjẹ alẹ..
wikipedia
yo
Wọ́n tún lè lò ó pẹ̀lú gàárì gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ ọ̀sán..
wikipedia
yo
wọ́n ti sọ Moi-Moi di irọrun nipa tita ẹwa Gberefu ni àwọn ilé ìtajà, ti o jẹ́ pe a ko ni ma rẹ ẹwa ṣókí mọ́ tabi lo agbara lati ma bọ̀, ki a ti yi po mọ́ omi ati àwọn èròjà rẹ ti a ti dárúkọ ṣaaju.àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
‘Ekuru jẹ́ oúnjẹ tó wọ́pọ̀ láàárín àwọn ẹ̀yà Yorùbá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Erèé tí wọ́n bo epo ara ẹ ni wọ́n maa ń lọ fi ṣe ekuru.O farapẹ́ mọ́in-mọ́in nítorí pé erèé tí wọ́n bo ni wọ́n fi ń se àwọn méjèèjì..
wikipedia
yo
Ìyàtọ̀ tó wà láàárín àwọn méjèèjì ni pé Moi-Moi máa ní àwọn èròjà mìíràn bí i ata, epo, ẹja, edé, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ nínú kí wọ́n tó sè é, wọ́n kàn máa wé ekuru sínú ewé lásán ni tàbí kí wọ́n ro ó sínú agolo (gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe ń ṣe Moi-Moi) kí wọ́n tó ṣe é.Bí wọ́n ṣe ń ṣe Moi-Moi náà ni wọ́n ṣe ṣe ekuru ṣùgbọ́n wọn kì í fi èròjà sí ekuru bí wọ́n ṣe ń Fisifì Moi-Moi..
wikipedia
yo
Àwọ̀ funfun ni ekuru máa ni, adùn rẹ̀ sì dàbí ọbẹ̀ díndín..
wikipedia
yo
Ó máa ń lọ dáadáa pẹlu ẹ̀kọ.Ekuru máa dùn ún jẹ pẹlu ọbẹ̀ díndín..
wikipedia
yo
Àwọn mìíràn máa gbádùn rẹ̀ pẹ̀lú Èkó, bẹ́ẹ̀ ni àwọn kan máa ń jẹ pẹ̀lú ẹ̀bá tàbí ọbẹ̀ ilá.Oúnjẹ yìí wọ́pọ̀ láàárín àwọn ará ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.Àwọn èròjà àwọn èròjà tí a tọ́jọ́ sí ìsàlẹ̀ yìí ni wọ́n ń lò láti pèsè ekuru tó dáa.
wikipedia
yo
Erèé ororofun ata díndín tamati alubo Maaji ìsebẹ̀ abbl.Awon itọkasiExternal yááfì Yuntunmi-an..
wikipedia
yo
Afihan (tabi Afihano, foofoo, FouFou) je okan lara awon ounje ti o gbajumọ ni iwo oorun Afrika..
wikipedia
yo
Páá pàà jùlọ Ghana àti Nàìjíríà, wọ́n tún ma ń ṣe ní àwọn orílẹ̀-èdè bí Sierra Leone, Guinea, Liberia, Côte d’Ivoire, Benin, Togo, Cameroon, The Democratic Republic of Congo, The Central African Republic, the Republic of Congo, Angola àti Gabon..
wikipedia
yo
Oríṣi ọnà ni wọ́n lè gbà ṣe Fùdún.fùfù ní ilé AFRIjà oníṣòwò orílẹ̀-èdè Portuguese ni wọ́n mú ẹgẹ́ wá sí ilẹ̀ Afrika lati orílẹ̀-èdè Brazil ní 16th Century..
wikipedia
yo
Ní Ghana, fùfù(tí wọ́n tún mọ̀ sí fùfùó), funfun, ó sì ma ń le (tí wọn kò bá fi ọ̀gẹ̀dẹ̀ sára ègé náà tí wọ́n bá ń gun lódò)..
wikipedia
yo
ọ̀ná tí wọ́n fi ń jẹ́ fùfù ní bíbú díẹ̀ ṣòwò tí wọ́n ó sì yí mọ́wọ́ láti mú ara rẹ̀ dán, wọn ó ti bọ ọbẹ̀ kí wọn ó tó jẹ.fùfù Nàìjíríà ní Nàìjíríà, fùfù tàbí Akpù jẹ́ oúnjẹ tí ó gbajúmọ̀, tí wọ́n sì ma ń fi ẹ̀gẹ́ ṣe..
wikipedia
yo
Akpù(bi àwọn Igbo ṣe ma ún pẹ́ ẹ) jẹ oúnjẹ tí wọ́n ma ń fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́ ṣe, wọ́n sì ma ún sábà jẹ pẹ̀lú ọbẹ̀ ẹ̀gúsí.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Tuwon shinkafa je okan lara awon ounje Naijiria ati Niger ti o wa lati Niger ati apa ariwa orile ede Naijiria ..
wikipedia
yo