cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Lẹhin ijàkàdi, ó ṣe àlàyé pé ara ohun ni kò yá, ó fi àpá han, pé nitori eyi ni ohun ṣe bẹ ọ̀rẹ́ ohun Ìjàpá ki ó bá ohun gbé ẹmu lọ fún wọn..
wikipedia
yo
wọn ṣe àlàyé ohun tí ìjàpá tí ó pè ní ọ̀rẹ́ rẹ̀ ṣe fún wọn..
wikipedia
yo
ará-ọ̀run dariji Ògbójú-ọdẹ pẹ̀lú ikilọ pe ki o maṣe gbára lé ọ̀rẹ́.Èkó inú ààlọ́ọpọlọpọ ọ̀rẹ́ kò ṣe é fi inú han, nítorí pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀tá lo n ṣe bíi ọ̀rẹ́ nitori àtijẹ.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Oòrùn ati òṣùpánígbà ìwáṣẹ̀, ọba òde ọ̀run níṣẹ́ kinni ohun gbogbo, ìkáwọ́ rẹ̀ sì ni gbogbo ohun tí a dá wà.Ọba òde ọ̀run ni iyawo , òṣì tún bí ọmọ meji..
wikipedia
yo
Ọ̀run ati òṣùpá fẹ́ràn ara wọn gidigidi, tí ó jẹ́ wípé bí òṣùpá ò bá sí nílẹ̀ ọ̀run kọ́ni jẹun àfi ìgbà tí òṣùpá bá dé ,bẹ́ẹ̀ no sì ni òṣùpá bí ọrun kò bá dé kò ní jẹun.Ní ọjọ́ kan ọba òde ọ̀run ránṣẹ́ sí òṣùpá ati ọrun ọmọ rẹ̀ wípé kí wọ́n wá rí ohun..
wikipedia
yo
Nígbàtí wọ́n dé bẹ̀ , ọba òde ọ̀run sọ fún wọn wípé òhun fẹ́ rin ìrìnàjò kan tí yóò sì pé kí ohun tó padà , òní kí òṣùpá àti ọ̀run lọ fi oríkòrí kí wọn ṣe àpérò ẹni tí yóò délẹ̀ dé ohun tí òhun bá wà ní ìrìnàjò..
wikipedia
yo
Wọ́n dúpẹ́ lọ́wọ́ baba wọn, wọ́n sì ṣe ìlérí láti ṣe gẹ́gẹ́ bí baba wọn ti sọ.Ní ọjọ́'rú ọ̀sẹ̀ kan náà, òṣùpá àti ọrun fi ojú kàn rà, ṣùgbọ́n oró ó wọ̀ láàrín àwọn méjèèjì lérí ẹni tí yóò délé nígbàtí baba wọn bá lọ..
wikipedia
yo
Òṣùpá ni ohùn oko ẹgbàágbèje ìràwọ̀ ni yóò délẹ̀ dé bàbá àwọn, bẹ́ẹ̀ni ọ̀run tutọ́ sókè fojúgbàá wípé ohun ìmọ́lẹ̀ ọmọ aráyé ni yóò delé de bàbá àwọn , òní láì sí ẹ̀mí ọ̀run inú òkùnkùn biribiri ní ayé kò bá wà,ó ní ẹ̀mí àfi ojojúmọ́ dára bí egbin, òṣùpá sọ wípé tí ó bá rí bẹ́ẹ̀ ọmọ aráyé òní máa sọ wípé iṣẹ́ lo òṣùpá ṣe lájùlé ọrun, òní ọ̀hún ni yóò delé de bàbá wọn.Bí wọ́n ti ń gba ọ̀rọ̀ náà bí ẹní gba igbá ọtí rẹ̀ ,títí ó fi di ìjà..
wikipedia
yo
Òṣùpá lu ọ̀run ni ìlù ẹni lu bàrà, ọrun náà sì lu òṣùpá bákan náà.Nígbàtí baba wọn gbọ́ sí ọ̀rọ̀ náà inú rẹ bàjẹ́,òní kí wọn pe àwọn méjèèjì wá sí àgbàlá Olódùmarè,ní ibẹ̀ ló ti jẹ́ kóKòjọ wọ́n wípé ohun ọba òde ọ̀run ni ṣe alákọ́so ọ̀sán àti òru,òní ni ìdí èyí ọ̀hún yóò pín ìlú náà sí méjì,òní kí òṣùpá máa jọba lérí òru , òsì ni kí ọ̀run máa jọba lórí ọ̀sán wọn kò sì gbọdọ̀ fi ojú kàn rà gẹ́gẹ́ bí ìjìyà ẹ̀sẹ̀ wọn.Ní ọjọ́ yìí inú òṣùpá àti ọ̀run bàjẹ́ nítorí wọ́n kọ́ni fọ́ jú kan rá mọ́ àti wípé ayé àti má ṣe bí ebi ti dópin..
wikipedia
yo
Ìgbà kúgbà ti ọ̀run àbí òṣùpá bati rántí ìdájọ́ yìí ,lọ́dọọdún wọn a máa sunkún lọ́pọ̀lọpọ̀ ,ẹkún wọ̀nyí ni àwa ọmọ ènìyàn npè ni ọjọ́...
wikipedia
yo
Àlọ́ ooooÀlọ́ ooooalo yìí dá lóri ikùn àti ẹkùn ìlú àwọn ẹranko, kìnnìún ni ọba wọn..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọjọ́ kan, ọba ẹranko pe gbogbo àwọn ẹranko jọ, ó sọ fún wọn pé òun fẹ́ dá ọjọ́ tí àwọn ẹranko yóò wá ṣe ère fún òun..
wikipedia
yo
Ó sọ pé ẹni tí ó bá lu ìlù dáadáa òun yóó dá lọ́lá..
wikipedia
yo
gbogbo àwọn ẹranko gbọ́ ọ̀rọ̀ ọba, wọ́n darí lọ sí ilẹ̀ wọn..
wikipedia
yo
Ẹnì kọ̀ọ̀kan nínú àwọn ẹranko n gbìyànjú a ti kan ìlú..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n dípò kí ẹranko kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ikùn ó kan ìlú tiẹ̀, ní ṣe ni ó lọ gbé ìlú ẹkùn níbi tí ẹkùn gbé e sí..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọjọ́ aré, ẹkún jí ní kùtùkùtù ó lọ dúró ní ọ̀nà tí ó lọ sí ilẹ̀ kìnnìún ọba ẹranko..
wikipedia
yo
Bí ẹranko kọ̀ọ̀kan bá ti fẹ́ kọjá ni ẹkún yóò yọ sí i tí yóò sì sọ pé kí ó lu ìlú rẹ̀ kí òun gbọ́..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó kan ikùn láti kọjá, ẹ̀rù ti bẹ̀rẹ̀ sí baà..
wikipedia
yo
Ẹkún gbá tètè,ṣùgbọ́n bí ẹkùn ṣe ní kí òun ó ki ikun mọ́lẹ̀ ni ó sá wọ inú ihò lọ..
wikipedia
yo
Ikún kò lọ láì f'arapa, èékánná ẹkùn ha ikún ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì..
wikipedia
yo
Bí eniyan bá rí ikùn lónìí, yóo rí pé ilà funfun wà ní ẹ̀gbẹ́ mejeeji ikùn di òní olónìí yìí o..
wikipedia
yo
PRIAR ìjàpá ati Atiyin oooo ààlọ̀ mi dá fírínu, ó dá lórí ìjàpá àti ọmọdékùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ àtilola..
wikipedia
yo
Ní ìgbà kan, ọmọdékùnrin kan wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ àtilọ́la ..
wikipedia
yo
Àwọn òbí rẹ̀ fẹ́ràn rẹ̀ gidigidi nítorípé òun nìkan ni wọ́n ní ..
wikipedia
yo
Wọn kò sì fi ohunkóhun duu; ṣe ni wọ́n máa nṣe ní ohun ẹlẹgẹ́; wọn kì í fẹ́ kí ẹnikẹ́ni bá a wí bí ó tilẹ̀ hùwà tó burú ..
wikipedia
yo
Nítorí ìdí èyí atilọ́lá máa ńṣe iṣẹ́ ọmọ oníbàjẹ́ , kì í sì gbọ́ràn sí ẹnikẹ́ni lẹ́nu ..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kan ní ìgbá àárò ọjọ́ , àtilọ́la ni òun fẹ́ lọ ṣeré pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ òun ní ojúde , ìyá rẹ̀ sọ wípé kó má ṣe jíjìjì lọ síbẹ̀ ..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ , àtilọ́lá kò ti ikùn sí àmọ̀ràn ìyá rẹ̀ ó sì wá àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ lọ ..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó dé ọ̀dọ̀ àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ , ó ṣeré lọ sí àfonífojì láti lọ wá oyin..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n bí ó ṣe wo àfonífojì ni wọ́n rí pé ọjọ́ ti ṣú ní ojú ọ̀run , ààrá sì bẹ̀rẹ̀ sí sán, ‘Tálíà
wikipedia
yo
Ọ̀kan nínú àwọn ọ̀rẹ́ àtiLọlá dábàá wípé káwọn padà lọ sílé kí òjò tó bẹ̀rẹ̀ sí í rọ̀ ..
wikipedia
yo
Àwọn èèyàn rí i pé àbá yìí dára , wọ́n sì múra láti padà, ṣùgbọ́n àtilọ́la sọ pé , ‘Èmi ó ní padà ní tèmi o, oyin ni mo wà débi èmi ó sì ní kúrò níbí láì ròyìn’báwo la ṣe fẹ́ rí oyin nínú òjò yìí?’ Ọ̀kan nínú àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ béèrè ..
wikipedia
yo
b'O ò bá lè rí oyin nínú omi, èmi ó dúró tọjọ́ yóò fi dá ..
wikipedia
yo
bí àtilọlá ti parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ ní ọjọ́ bẹ̀rẹ̀ sí fọn ..
wikipedia
yo
...Wọ́n padà sí abúlé wọn sì fi òun nìkan sílẹ̀ kò máa wá oyin..
wikipedia
yo
Láìpẹ́ , òjò bẹ̀rẹ̀ sí rọ̀ , ó sì bẹ̀rẹ̀ sí di adágún omi kékeré .Àtikàn ńfò síhìn-ín ń ṣohun-un bí alágẹmọ , ó ńjuwọ́ sókè , sílẹ̀ ó sì ń fọwọ́ gbé omi..
wikipedia
yo
Àwọn àgbẹ̀ tó ń padà lọ sílé látinú oko sọ fún pé kí ó kúrò nínú òjò kí ó máa lọ sínú abúlé ..
wikipedia
yo
Ṣugbọn níṣẹ́ ni ọmọ aláìgbọràn yìí fẹ́ ojú mọ́ wọn , ó ń yọ ahọ́n sí wọn , ó sì ń fi wọ́n ṣe yẹ̀yẹ́ , ó sì ń jó ninu adágún omi bí òjò tí ń rọ̀ síi ..
wikipedia
yo
L àìpé àgbàrá òjò gba gbogbo àfonífojì, àtilọ́la kò sì rí ibi tí ó lè sọkún, ó rí igi ọdán kan tí ó lọ sí abẹ́ rẹ̀ ..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n bí ọjọ́ yìí ti ń pọ̀si, àtiÈnìyàn pinnu láti gun igi lọ kí agbára òjò má ba à gbé e lọ ..
wikipedia
yo
Ní kété tí ó fẹ́ máa gun igi yìí ni ó kọsẹ̀ tí ó sì ṣubú sinu agbára tí omi sì bẹ̀rẹ̀ sí gbé e lọ ..
wikipedia
yo
àtilọ́la fi igbe ta, ṣùgbọ́n kò sí ẹni tó wà nítòsí ..
wikipedia
yo
Bí omi ṣe ń gbé e lọ , ó rí àwọn igi wẹẹrẹ àti igi títóbi , ó sì nawọ́ gán àwọn igi, ṣùgbọ́n nítorí àwọn igi náà léfò lórí omi, kò wúlò fún.Àtila ṣe àkíyèsí ilé, ó sì í kígbe ní ohùn rara, ‘Ẹ gbà mí ooo, ẹ Jôko , ẹ ràn mí lọ́wọ́,’ ó n ké sí onílẹ̀ náà kí ó ràn òun lọ́wọ́ ; ìjàpá ni ó ń gbé inú ilé yìí o sì fèrèsé rẹ̀ , ó rí àti Lọlá ti odo ń gbẹ lọ..
wikipedia
yo
Ní kíá ó bọ́ sóde , ó mú igi gígùn kan tí ó wà ní ojúde rẹ̀, ó sì náà sí àtilọ́la ..
wikipedia
yo
Ọmọ náà gbá igi yìí mú dan-in-dan-in bí ìjàpá ti fàá kúrò nínú omi..
wikipedia
yo
Bí ọmọkùnrin yìí ti jàjàbọ́ , ìjàpá mú wọ ilé rẹ̀ , ó dá iná fún láti yà, ó sì fún ní òun jíjẹ , ṣùgbọ́n ìjàpá ọlọ́gbọ́n èwe kìí ṣoore fún ni láì sìrègún ..
wikipedia
yo
Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ronú ohun tí òun lè rí gbà lọ́wọ́ ọmọ náà ..
wikipedia
yo
Ní gẹ́rẹ́ ti ọmọ náà jẹun tán , ó mú orin b'ẹ́nu ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọrin eléyìí tí ìjàpá kò gbọ́ ..
wikipedia
yo
Ohùn ọmọ naa dùn gbọ́ leti , ó jẹ́ orin olóhun gbọ̀ọ̀rọ̀ ; orin ti ìyá àtilọ́la máa nkọ fún..
wikipedia
yo
Orin na lọ bayi pe,orin ààlọ̀=ọmọ ò, ẹ̀ II pè dàgbà ọmọ o, ẹ̀ í pè dàgbà aọmọ o....Bí ọmọ náà ti kọrin tán , ọmọ náà sùn ..
wikipedia
yo
Ìjàpá si ń ronú pé , ‘Kíni mo le ṣe?’ Ìjàpá sì lọ ṣíbí ti ọmọ náà sùn sí , ó bẹ̀rẹ̀ sí lu ìlù ńlá kan..
wikipedia
yo
Nigba ti o di ojo keji ti ọmọ naa ji, ìjàpá pe e o ni ki o joko sinu ilu naa ..
wikipedia
yo
Ọmọ náà dáhùn pé, Èé ṣe tí èmi ó fi jókòó sínú ìlú ?’ Ìjàpá ni, pẹ̀lú oore ńláǹlà tí mo ṣe tí mo gbà ọ́ lọ́wọ́ ikú, ṣe ó yẹ kí o má a bí mi ní béèrè - kí béèrè..
wikipedia
yo
Ọkàn wọn pọ̀ rúurú, nítorí ọmọ náà kò padà wálé nígbàtí ọjọ́ dá..
wikipedia
yo
Wọ́n wá rìn lọ ààfin wọ́n sọ fún ọba pé ọmọ àwọn ti sọnù , wọn kò rí.Bayi ni ọba rán àwọn oníṣẹ́ ọba láti wá..
wikipedia
yo
Nitorina wọn pada lọ jábọ̀ f'ọba wípé àwọn kò rí.Ìjàpá kò mọ̀ pé wọ́n nwá ọmọ yí..
wikipedia
yo
Ṣugbọn o bọ́ sí ààrin ọja o ni,‘Ẹ wá wọ ìlú ti ń kọrin , ìlú àràmọ̀ǹdà ‘Ẹ wá wọ ìlú ti paniyan, ìlú àràmọ̀ǹdà ’ẹ wá wo ìlú yí ọ, àràmọ̀ǹdà ni..
wikipedia
yo
Àwọn èèyàn sì bẹ̀rẹ̀ sí jó , wọ́n nsọ gẹ́lẹ́ àti fìlà wọn sílẹ̀ ..
wikipedia
yo
Wọ́n jọ jọ jó títí ó fi rẹ̀ wọ́n, wọ́n dá owó sílẹ̀, wọ́n sì fún ìjàpá ní owó gọbọi nítorí ìlú àràmọ̀ǹdà yìí..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kejì ọba ránṣẹ́ pe ìjàpá , ó ní kó wà pẹ̀lú ìlú rẹ̀ sí ààfin òun..
wikipedia
yo
Nígbà tí ìjàpá dé ‘bẹ̀, ẹnu yáa láti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn tí wọ́n jókòó, inú rẹ̀ dùn lọ́pọ̀lọpọ̀.Ó sọ fún ọba pé òun kò le lu ìlù láìgba owó, ó ya ọba lẹ́nu láti gbọ́ èyí, ṣùgbọ́n ó fún ìjàpá ní àpò kan nítorí ó fẹ́ gbọ́ ìlú tí wọ́n ń sọ..
wikipedia
yo
Báyìí ni ìjàpá gba ìlú lórí mọ́lẹ̀ tí ọmọ yìí sì bẹ̀rẹ̀ sí níí kọrin, ọmọ o, ẹ í pè dàgbà ‘Ọmọ o, ẹ̀ í pẹ́ dàgbà ,’ó kọrin náà gbogbo ènìyàn bẹ̀rẹ̀ sí ní jó, ọba àti àwọn ìjòyè rẹ̀ jọ jọ jó títí ó fi rẹ̀ wọ́n..
wikipedia
yo
Bí ọba ti ń jó, ó ṣàkíyèsí ìyá àtilọ́la tí ó jókòó sí kọ̀rọ̀ tí ó ń sunkún, inú bí ọba, ó ní kí wọn pe baba àti ìyá àtilọ́la wá sí iwájú òun, nígbà tí wọ́n dé ọ̀dọ̀ ọba wọn ní ìlú tí ìjàpá ń lù kìí ṣe ìlù lásán, ọmọ òun lọ ń kọrin nínú ìlù náà, kò sí ìyá tí yóò gbọ́ ohùn ọmọ rẹ̀ tí kò níí tẹ etí, ọba pàṣẹ kí gbogbo ìlú jókòó, ọba ní kí wọ́n fa ìlú náà ya..
wikipedia
yo
Ni atilola ba jade ninu ilu, bi o ti ri awon obi re ni o sare fo mo won, oba ni ki won gbe ìjàpá si ewon, ìjàpá ni oun ni oro lati so, o ni oun ni oun gba omo yen nigbati agbara ojo n gbe lo, oba ronú si oro ti ìjàpá so yìí, sugbon pelu ikilo pe enikeni ko gbọdọ dan iru re wo mo, oba paṣẹ ki ìjàpá da owo owo re pada ni iko, ìjàpá si gbe owo naa jade o dàá pada fun Kábíyèsí.Ẹ̀kọ́ inú aáloo se pataki fun awon omode lati ma a gbọran si awon obi won lenu..
wikipedia
yo
nítorí ẹ̀kọ́ ti àtilọ́lá tí kọ́ yìí, ó mú ẹ̀kọ́ náà lọ, ó sì di akíkanjú ọkùnrin...
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Èkó ni agbègbè ìṣàkóso marun, èyíinì ni, Ikorodu, Ikeja, Epe, Badagry, àti Lagos Island, tí Ikeja sì jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Àwọn agbègbè ìṣàkóso àti ìdàgbàsókè márun yí ní àpapọ̀ ní àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ogún (20) àti àwọn agbègbè ìṣàkóso (mẹ́tàdínlógójì)37 (LCAs)..
wikipedia
yo
Awon agbegbe isakoso ati idagbasoke yi ni Agba/oke-Odo, Agboyi-Ketu, Ayobo-Ipaja, Bariga, Egbe-Idimu, Ejigbo, Igando-Ikotun, Ikosi-Isheri, Isolo, Mosan-Okunola, Odi Olowo-Ojuwoye, Ojodu, Ojokoro, Onigbongbo and Orilẹ Agege.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Holy Child College jẹ ile -iwe girama ijo Catholic fun awọn ọmọbirin ni ipinlẹ Eko, Naijiria..
wikipedia
yo
A da kalè ni ọjọ 9 Oṣu Kẹrin ọdun 1945 nipasẹ Society of the Holy Child Jesus (SHCJ) ati ṣiṣe nipasẹ Archdiocese Roman Catholic ti ipinlẹ ti Eko ..
wikipedia
yo
O wa ni Guusu-Oorun Ikoyi ti o wa ni eti Obalende ati Keffi; lẹgbẹẹ ile-iwe arakunrin rẹ St Gregory's College, Lagos ..
wikipedia
yo
Holy Child College ni ipin ọdun mẹta ti akoko Ile-iwe Junior (JSS) ati ọdun mẹta ti ile-iwe agba (SSS).itan a da ile-iwe naa kale ni 9 Oṣu Kẹrin (April 9) ọdun 1945 pẹlu awọn kilasi meji ti awọn ọmọbirin 15 kọọkan ati awọn olukọ mẹrin..
wikipedia
yo
Lati mu nọmba awọn ọmọ ile-iwe pọ si, wọn bẹrẹ si un gba awọn alẹko tuntun si kilasi kini ni ọdọdún..
wikipedia
yo
Yo ṣe di a ìgbà ti àwọn ọmọ ilé-ìwé ti o báwọn bẹrẹ ni Jss pari ẹkọ iwe mẹfa wọn, àwọn akọ-ẹkọ ile-iwe naa ti pọ lati 30 si 200(ọdun 1950).Awọn Alakoso ati àwọn Alakoso ọdun 1945-1956 - ifiweranṣẹ..
wikipedia
yo
Antoinette Oparaawon eniyan ti o ti gba ile-iwe naa jade Joke Silva, oṣere Naijiria, oludari, ati obinrin oniṣowo Margaret Dada Marquis (1944-2022) +, ti gba idanimọ gegebi ọkan ninu awọn aṣáájú-ọna obirin ti o jẹ aṣáájú-ọna Naijiria Tọ́kì Myipadagun, Aare obinrin Kẹta ti Lagos Chamber of Commerce and Industry Francesca Yetunde Emanuel, Iranṣẹ gbogbo Eniyan Julie Coker, akọ̀ròyìn tómi Somefun, CEO ti Unity Bank PLC Yvonne Ekwere Sokari EKine, Fotogira, Iggaga, onímọ Èkóàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Infobox road gbigbẹ Trakópa CateGoryin road gbigbẹ for WikiGbota “TiìyeBox Road Tọchi In Nigeria Eko Eko- Ibadan jẹ opopona ti o gun to ti o so Ibadan, olu ilu ipinle Oyo pẹlu Eko, Ilu tótóbito orilẹ-ede Naijiria..
wikipedia
yo
ó tún jẹ́ ọ̀nà pàtàkì sí àríwá, gugúsù àti àwọn ẹ̀yà ila-oòrùn ni Nigeria..
wikipedia
yo
ọ̀nà òpópónà jẹ́ èyí tí a kọ́kọ́ ṣe ní Nàìjíríà, tí a ṣe ní oṣù kẹjọ ọdún 1978 lakoko àkókò ológun, lábẹ́ ìṣàkóso Lieutenant-General Olusegun Obasanjo ..
wikipedia
yo
Opopona naa jẹ ọkan ninu awọn opopona laarin ipinle si ipinle ti awon eniyan n run julọ ni Naijiria, awọn oko ti o un gba ibè lojumọ ma un le ni 250,000, o si je si opopona ti o tobi julọ ni Afirika..
wikipedia
yo
ó ara àwọn iṣẹ́ tí ṣe AFederal Road Maintenance Agencyral (Fer má ún tún ṣe laarin ipinlẹ si àjo tí òun ma ún sọyé ojú ọ̀nà ṣe tí òun ma ma ún ṣe larin a larinnipinle sí Ìpínlẹ̀ ti Nigeria . Ni July 2013, Aare Goodluck Ebele Jonathan Ààrẹ orile-ede Naijiria nígbà náà kede àtúnse ọ̀nà náà, Aare Goodluck sọ pé yó din akoko ti àwọn ènìyàn n lọ lójú ọ̀nà kù..
wikipedia
yo
ilé-iṣẹ́ Julius Berger Nigeria ati Reynolds Construction Company Limited ni wọn gba iṣẹ́ naa owó àtúnse rẹ ni bilionu 167 Naira, owo ti o jẹ 838,986,290 dọ̀la nigba naa..
wikipedia
yo
Àwọn apá méjì ti òpópónà náà ni wọn yóò tún ṣe, apá kini (Lagos si Interchange Sagamu) ati apa keji (iparọpo Sagamu si Ibadan).Àwọn Ìtọ́kasí Ibadan..
wikipedia
yo
Àlọ́ ooooalo ni ayé àtijọ, ìgbín àti ìjàpá jé ọ̀rẹ́ kòríkòsùn..
wikipedia
yo
Gbogbo ìlú ló sì mọ̀ wọ́n papọ̀ pé ọ̀rẹ́ gidi ni wọ́n ń ṣe..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ìwà ìjàpátìrókò ọkọ yánníbo ọ̀dàlẹ̀ pátápátá ni.Ní ìlú tí ìgbín àti ìjàpá ń gbé, ìṣẹ̀lẹ̀ kan ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ kan..
wikipedia
yo
Bí Ìjàpá ti gbọ́ pé àwọn kan ti pa abuké ọ̀sìn, ni ó bá lọ sí ọ̀dọ̀ ọba láti lọ sọ fún un pé ọ̀rẹ́ òun ìgbín ni ó pa abuké ọ̀sìn..
wikipedia
yo
Ọba bi ìjàpá bóyá ohun tí ò sò dáà lójú dáadáa á bí eré ló ń ṣe.ìjàpá sọ fún ọba bí òun àti ìgbín ṣe jé ọ̀rẹ́ kòríkòsùn àti bí àwọn kì í ṣe fi nǹkan kan pamọ́ fún ara wọn..
wikipedia
yo
Ìjàpá fi kún ọ̀rọ̀ rẹ̀ pè ìgbín fúnra rẹ̀ ló wá sọ fún òun pé òun ni òun pa abuké ọ̀sìn..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n mú dé ọ̀dọ̀ ọba, ọba bi ìgbín léèrè bóyá òun ni ó pa abúlé ọba..
wikipedia
yo
Ìgbín dá ọba lóhùn pé kì í ṣe òun ni òun pa abuké ọba àti pé bí ọba bá fẹ́ mọ ẹni tí ó pa abuké ọba òun lè ran ọba lọ́wọ́ láti jẹ kí ó mọ ẹni tí ó pa á.Nígbàtí ọba gbọ́ báyìí, ó pàṣẹ pé kí wọ́n tú ìgbín sílẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí wọ́n tú ìgbín sílẹ̀ tán, ó sọ fún ọba pé láti mọ ẹni tí ó pa abuké ọba wọn ní láti fún òun ní ẹṣin ńlá kan àti àwọn onílù..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ yìí kò kọ́kọ́ yé ọba ṣùgbọ́n nígbà tí ìgbín ti fọwọ́ sọ̀yà pé òun yíò fi ojú ẹni tí ó pa abuké ọba hàn, ọba kó jà níyàn ó ṣe bí ó ti wí..
wikipedia
yo
Nígbà tí ìjàpá gbọ́ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ inú rẹ̀ bàjẹ́ ó ń ronú pé òun ni ó yẹ kí ọba dá lọ́lá torí òun ni òún pa abuké ọba..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó dé ààfin ọba, ó kí ọba pẹ̀lú ìdọ̀bálẹ̀, ó sọ fún ọba pé òun ni ó yẹ kí ọba dá lọ́lá torí pé òun ni òun pa abuké ọba..
wikipedia
yo
Ó sì tún sọ fún ọba pé òun ni òun yẹ fún ọ̀la tí ọba dá ìgbín torí pé òun ni òun pa abuké ọba..
wikipedia
yo
Kíá ni ọba ní kí àwọn ẹmẹ̀wà òun mú ìjàpá kí wọ́n dìí Tápà tẹsẹ̀ kí wọn ó ti ojú rẹ̀ yọ idà.Báyìí ni ìjàpá fi ẹ̀tanú àti ìwà ọ̀dàlẹ̀ pa ara rẹ̀ tí ìgbín sì ń jẹ ayé rẹ̀ lọ níbi tí ó tutù títí di òní yìí.Ìtàn yìí kọ́ wá wípé kò yẹ kí a máa ṣe ìlara ẹnìkejì wa...
wikipedia
yo
Eni-owo James Wilson Robertson jẹ́ òṣìṣẹ́-ìjọba ọmọ orílẹ̀-èdè tí ó ṣojú ìjọba Bíkoríkò lórílẹ̀-èdè Nigeria láti ọdún 1955 sí 1960.Ìgbésí-ayé rẹ̀ láti èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́ ó kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ìwé Merchiton Castle School ní ìlú Edinburgh àti Balliol College, Oxford..
wikipedia
yo
Ó ṣiṣẹ́ sin ìjọba Bìrìtì lẹ́ka tó ń mójú tó àwọn ológun, British army pẹ̀lú ẹ̀ka ọmọ-ogun Gordon Highṣíṣàṣàrò àti Black Watch..
wikipedia
yo
Wọ́n dá a lọ́lá oyè ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ - òfin, Doctor of laws láti University of Leeds lọ́dún 1961.Iṣẹ́ lẹ́yìn Oxford, ó dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ òṣèlú Sudan, Sudan Political Service ní ọdún 1922 sí 1953, bẹ́ẹ̀ náà ó ṣiṣẹ́ ní agbègbè ìṣèjọba Blue nílẹ̀, White nílé, Fung, àti Kordofan, bákan náà ó jẹ́ akọ̀wé ilé-iṣẹ́ ìjọba láti ọdún 1945 sí 1953..
wikipedia
yo