cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní àkókò yìí ni akọ̀wé-yányán àwọn orílẹ̀-èdè tí ìjọba Bìrìtì ń ṣàkóso, Ọ̀gbẹ́ni Oliver Lyyàrá ran-an sí British Guiana lóṣù kìíní ọdún 1954 láti ṣe àkọsílẹ̀ ìjábọ̀ ẹ̀sì Robertson Commission láti ṣe ìwádìí rògbòdìyàn tí ó bẹ́ sílẹ̀ nígbà náà látàrí ìdìbò tí ó gbé ẹgbẹ́-òṣèlú People's Progressive Party, tí wọ́n fẹ̀sùn kàn lásìkò náà pé wọ́n ti ń bá àwọn elétò ìṣèjọba aláṣepọ̀,Communist tí wọ́n ṣokùnfà fífagilé òfin fún ìgbà díẹ̀.Lẹ́yìn àṣeyọrí tó lôòrí tí ó ṣe, èyí ló mú wọn ran-an sí orílẹ̀-èdè Nigeria..
wikipedia
yo
Oun ni aṣoju ijoba Bìrìeli, ti o ṣoju Aare-binrin, Queen Elizabeth II ni Nigeria lati ojo kẹẹ̀ẹ́dógún osu kefa odun 1955 si ojo kerindinlogun, osu Kọkànlá odun 1960.Àbúrò rẹ ni Ian Robertson, Lord Robertson, ti ọmọ re, Sally fe Nick Kuenssberg ..
wikipedia
yo
Articles with Hcardbyyo Adedeji (1930-2018) ni a bini oṣu December ni Ijebu Ode je Economist ati Adèmí Omo orile ede Nigeria..
wikipedia
yo
Arákùnrin náà jẹ́ Comival ti Federal orílẹ̀ èdè Naigiria lórí Economic Development àti rẹ̀àṣekára láti ọdún 1971 dé 1975.Ìgbésí ayé arákùnrin náàarákùnrin náà gba oyè Professor nígbà tí ó ọmọ ọdún mẹ́rin dín lógójì..
wikipedia
yo
Ní oṣù June, ọdún 1975 ní Ayan Adebayo Adédèjì gẹ́gẹ́bí executive secretary tí United Nations Economic Commission fún ilé àfizũ tó sì wà ní ipò náà títí oṣù July ọdún 1991.Adedeji kò plan ti Action ti ìlú Èkó ti ọdún ọdún 1980 tí ún àti OAU sì tẹ́wọ́gbà.Nígbà tí arákùnrin náà padà sí ilẹ̀ náigiria ni ó dá Africa Center fún Development àti strategic Studies sílẹ̀ (ACSFIWFINí Oṣù December, ọdún 2010 nígbà tí arákùnrin náà pé ọmọ ọdún ọgọrin lẹ́yìn tó ti fẹ̀yìn ní ó lo ìyókù nínú ìgbésí ayé rẹ̀ ní ìlú rẹ̀ Ìjẹ̀bú-Òde ní Ìpínlẹ̀ Ògùn. Kú ní ìrọ̀lẹ́ osù April ní ọdún 2018 ní ìlú Èkó lẹ́yìn tó ṣe àìsàn ọlọ́jọ́ pípẹ́..
wikipedia
yo
Uneca ṣe ìrántí ologbe náà láti fi dádá ní oṣù July ọdún 2018.Àmì ẹ̀yẹ àti yíndẹ́jáde gba ìdánilo ti National ti commander ti Federal Republic.Àwọn Ọjọ́ìbí ni 1930..
wikipedia
yo
Joshua Selman nim ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ mo sí aposteli Joṣua Selman tabi àjs jẹ́ òjíṣẹ́ Ọlọ́run, elérò orin àti Onimọ-ẹ̀rọ kemikali ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun ni oludasile ati adari Ijo eterAtalaya Network International(eni), o si ma un dari isin kan ti àpèlé rẹ KInonia..
wikipedia
yo
Joshua Selman jẹ́ ọmọbíbí ìpínlẹ̀ Plateau.A bí Joshua Sellman ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1980 ni Jos, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O kẹkọọ gboye nipa imọ-ẹrọ kemikali ni ile-ẹkọ giga ti Ahmadu Bello ni Zaria, ni ilu Kaduna ni Naijiria.Iṣẹ iranṣẹselman beere ise iranse ni igba ti o wa ni Ile-ẹkọ giga, Todu ati awon ọrẹ rẹ ni won jo beere re..
wikipedia
yo
eterìkórè Network International(eni) ni oruko ise iranse re, won dada ni osu keta ni odun 2011, ni agboolé Zaria ni ilu Kaduna ni Nigiria.oti waasu kaakiri agbaye pelu ise ami ati agbara.Iṣẹ iranṣẹ naa pin eka si ilu Abuja ni Naijiria, ni odun 2021.Awon itọkasiawon Olukọwe ara Naijiria..
wikipedia
yo
Nígbà lailai Erin Òkè ati Ìjàpá je ore tímọtímọ, ìjàpá je agbe nigba ti Erin Oke je ògbójú ode Apẹran..
wikipedia
yo
Ìjàpá àti Erin a máa ṣe pàṣípààrọ̀ oúnjẹ ọkọ̀ bíi iṣu, ìkan ẹ̀gẹ́ ṣùgbọ́n kò tẹ́ ìjàpá lọ́rùn bíi kí erin òkè máa fún ni ẹran lọ́fẹ gẹ́gẹ́ bíi ọ̀rẹ́ àti àgbà..
wikipedia
yo
Bíi ìjàpá ṣe ń gba ẹran lọ́wọ́ erin òkè bẹ́ẹ̀ ló ń gba ẹja lọ́wọ́ erinmi..
wikipedia
yo
ní ọjọ́ kan, ìjàpá lọ bá erin òkè pé kí ó bá òun wá ẹran nlá kí òun fi ṣe àsè fún àwọn ẹgbẹ́ òun, lèyí tí òun ṣe tán láti fi ẹja nlá pààrọ̀ fún..
wikipedia
yo
Inú Erin Òkè dùn lati bá Ìjàpá wá ẹran nla fi pààrọ̀ fún ẹja ki òun lè jẹ nkan mìíràn yàtọ̀ si ẹran gbogbo ìgbà lai mọ pé Ìjàpá fẹ fi ìyà jẹ òun ni.
wikipedia
yo
Bákannáà, ìjàpá tún lọ bá erinmi pé kí ó fún òun ní ẹja ńlá kí òun fi ẹran ńlá pààrọ̀ fún..
wikipedia
yo
Erinmi fún ìjàpá ní ẹja bẹ́ẹ̀ ní erin òkè fún ìjàpá ní ẹran, ó sì dá ọjọ́ méje fún àwọn méjèèjì..
wikipedia
yo
Ìjàpá tòun taya àti àwọn ọmọ rẹ̀ nṣe bẹ́ẹ̀ni wọ́n sọ..
wikipedia
yo
Kí ọjọ́ méje tó pé, ó léwu i okùn àgbà tó yìí, ó gbẹ lọ fún ẹ̀rín òkè pé okùn náà ni yóò fi wọ ẹja nínú..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ ó sọ fún Erinmi pé òun ti wá Òkun tí yóò fi wọ ẹran láti òkè sínú omi..
wikipedia
yo
nígbàtí ọjọ́ méje pé, Ìjàpá mú Erin òkè lọ sí etí odò láti fa ẹja jáde nínú ibú, bákan náà ó wọ inú omi lọ láti so òkun mọ́ Erinmi lọ́rùn lát wọ́ ẹran sínú omi..
wikipedia
yo
Bí Ìjàpá ṣe kúrò ní ọ̀dọ̀ Erinmi, tí ó rìn sókè díẹ̀ ló ti sọ fún àwọn méjèèjì pé ó yá o..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ ni Erinmi ń fa ẹran láti òkè tí erin òkè sì ń ẹja láti inú ibú, gbogbo igi ń wò lókè bí erin òkè ṣe ń jà fitafita láti fa ẹja bẹ́ẹ̀ ni odò ń dàrú bí Erinmi náà ṣe ń jà láti fa ẹran sínú omi..
wikipedia
yo
Àwọn méjèèjì gbìyànjú títí di ọ̀sán kí erinmi tó sọ pé òun yóò gòkè lọ wo ẹran náà..
wikipedia
yo
Báyìí ni ó gan-an ni ọ̀rẹ́ rẹ̀ Erin òkè, wọn ki ara wọn pé ìjàpá ló dà á sílẹ̀, inú bí erin òkè ṣùgbọ́n ìjàpá ti sá sábẹ́ ìràwé..
wikipedia
yo
Erinmi padà sínú omi bẹ́ẹ̀ni erin òkè padà sílé tí ó sì pinnu pé òun kò ṣiṣẹ́ ọdẹ mọ́, bẹ́ẹ̀ ni kò jẹ́ ẹran mọ́, iṣẹ́ ọdẹ pípa ẹran lọ fìyà jẹ òun lọ́wọ́ ìjàpá..
wikipedia
yo
Ki a ma ṣe jẹ ki wọn fi dúdú pe funfun fun wa.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Oun ni oludasile opobo ti o wa ni Ipinle Rivers ni orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
Born in Umudúrúoha AmaIgbo in Present-day Imo State, ojo ibi rẹ ati awon obi re a ko mo.J gba Iyanda lowo oga re ni enu ise ati bi omo odo leyin ti o ti wa lenu ise naa fun odun ti o ti pe..
wikipedia
yo
Nígbà tí ọ̀gá rẹ̀ fẹ́ ṣe lọ́lọ́pọ̀, ó gba àmọ̀ láti lè maa dari okowo, lẹ́yìn tí ó sì dari ilé owó tí wọ́n ń pè ní Anna Ppple House ní agbègbè kan ní nínú Island lábébé rẹ̀ ní Annap Np gba àwọn ilé tí wọ́n ti ń ṣòwò títí ti ìjà fi wà láàrín wọn àti Manilla pép tí ọkọ̀ Jubo pàbo wọn sọ fún Jajà pé kí ní gbajú kúrò ní ìlú já mégun mékan ní ọdún 1869. ní ọdún tí ó gbajúrọ̀ ní owó epo..
wikipedia
yo
Jji gba Iyanda lati owo awon Eebo ati awon alawo dudu lati le ta epo, ni odun 1879 ni o bere si ni ta egberun mejo epo fun awon Eebo alawo funfun..
wikipedia
yo
bí ó ti lé jèpé òun àti àwọn òyìnbó aláwọ̀ funfun ní aáwọ̀, jàjà ri pe àwọn ọmọ rẹ̀ lọ ilé ìwé láti kẹ́kọ̀ọ́ ní Glasgow, tí ó sì gba àwọn Èèbó láti ṣiṣẹ́ ní ilé ẹ̀kọ́ kékeré tí ó í sí òpóbọ̀..
wikipedia
yo
Ó sì ṣe ìdinṣe àwọn Èèbó tí wọn ń kéde ìhìn rere láti ma wọ opóbọ.Ní ọdún 1884, ìpérọ ní orílẹ̀ èdè Berlin, àwọn ará ìlú yóò ṣọpẹ́ ọ̀pọ̀ jẹ́ agbègbè àwọn Èèbó ..
wikipedia
yo
Nígbà tí jàjà kóo láti dópin owó orí lọ́wọ́ àwọn Èèbó tí wọ́n ń ṣòwò, igbákejì Consul pe jàjà láti dùndúnra ní 1887..
wikipedia
yo
Wọ́n gbé jàjà nígbà tí ó bá ọkọ̀ èébì kan wọ̀lú ; èyí tí ó gbìyànjú ní Accra ní Gold Coast agbègbè àwọn Èèbó tí wọ́n n pè ní Ghana, tí ó gbéra, tí ó sì kọ́kọ́ wọ ìlú Londọnu tí ó wọ̀ Saint Vincent àti Barbados ní British West Indies ó dé West Indies ni wọ́n fẹ̀sùn kàn pé ó dáa rògbòdìyàn sílẹ̀ láàrin àwọn aláwọ̀ dúdú tí ó wà níbẹ̀, èyí tí wọ́n sì n bínú sí bó ti ṣe ń darí àwọn aláwọ̀ dúdú ní Ọ̀pọ̀bọ̀, èyí tí òṣì àti ìyáa ń jẹ́ àwọn aláwọ̀ dúdú.Ní ọdún 1892, wọ́n fún jàjà ní Ìyàndá láti padà sí ìlú Anlábọ̀, ṣùgbọ́n ó di aláìsí nígbà tí wọ́n ń bí wa sílẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà lọ ìlú Èèbó àti bi o ti pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ ni agbára àti pàṣẹ rẹ̀ ti ń dínkù..
wikipedia
yo
ní ọdún 1903, wọ́n gbẹ́ ère kan kí wọ́n má ṣe gbàgbé ọba Jiya ilu Opóbo ni aarin ilu Opóbo.Ẹ wó Gengen of AFRIOC itọkasiiko sile sile Stateking J of opo at Black History Pages of Odunbo-ama (opo town) at ìgbani-awo Association, a barbadian Folk Song Refẹrẹncing the King1821 births1891 deaths from opo opo-century Nigerian Businesske Monadie of àwùjọ Nigeria Ọ̀wọ́-Century Mona in Africa..
wikipedia
yo
Awọn lijàdú Sisya ( bibi Ọjọ mejilelogun Oṣu Kẹwa Ọdun 1948), Taiwo ati Kehinde lijàdú (won ku ni ojo mẹsan osu mokanla odun 2019), awon mejeeji je ibeji ti won jọra gidi gan-an, won je omo Nigeria ti won je awon olorin ibeji Nigeria lati arin ọrun odun 1960 titi di ọrun odun 1980..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe àṣeyọrí ní Nàìjíríà àti nipé wọn ní ipa pàtàkì ní ìlú Amẹ́ríkà àti Yúróòpù..
wikipedia
yo
Eka tí wọ́n fi mọ́ àwọn nipé wọn jẹ́ ẹ̀yà àwọn ìbejì Pointer West Afrika,wọ́n máa da orin Afro pẹ̀lú Jazz àti Disco pọ̀ sí orin kan, láti orísun kan, Ṣíṣú mọ́ òpin ọ̀run ọdún 1980,wọ́n fẹ̀yìntì láti orin kíkọ ..
wikipedia
yo
Wọ́n jẹ́ ìbátan sí akọrin olókìkí Fela Kuti.Iṣẹ́ àwọn ìbejì na dàgbà ní Ìbàdàn Nàìjíríà,Àwọn olórin yí jé àwòkọ́ṣe fún wọn nígbà tí wọ́n dàgbà arétha Franklin, Victor Ọláìyá àti Miriam Makeba.ẹ̀rọ orin Lemmy Jackson jẹ́ ìtọ́sọ́nà fún àwọn méjèèjì àti ní Tog ná ni wọ́n tọ́ka sí tó ràn lọ́wọ́ ní àṣeyọrí...
wikipedia
yo
Folashade Tolulope Ogunsola eni ti won bi ni odun 1958 je ojogbon ninu imo Medical Microbiology, oun si ni alákòóso agba fun ile-eko Yunifasiti ilu Eko lasiko ti a n ko apileko yi..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ onímọ̀ nípa bí à n kojú àrùn pàá pàá jùlọ kòkòrò àrùnHIV/AIDS..
wikipedia
yo
Ogunsola ti kọ́kọ́ di ipò alákòóso àgbà (provosti) ti Ile-ẹkọ imọ iṣẹgun Oyinbo ti (College of Medicine) ti Yunifásítì ìlú Èkó mu rí, oùn sì ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ di ipò náà mú..
wikipedia
yo
O tun wa lara awon igbakeji adari ti Yunifasiti naa, ipo ti o di mu laarin odun 2017 si odun 2021.A fi si adilémú ipo adari Yunifasiti ipinle Eko ni ojo kẹrinlelogun osu kejo(24 August) odun 2020) leyin igba ti won yo ojogbon oluwatoyin Ogundipé ni ipo adari ile-iwe naa..
wikipedia
yo
Ni ojo keje osu kewa(7 Oct 2022), a yan OgunShola gege bi adari ile-iwe naa, oun si ni obinrin akoko ti o di ipo naa mu.ibẹrẹ aye ati Eko rẹwọn to Ogunsola dagba ninu ile-eko Yunifasiti iluIbadan nibi ti baba ti baba re, Akin ti je oluko Ode..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó wà ní ọmọdé, ó ma ń ṣe bí àwọn onímọ̀ òyìnbó pẹ̀lú bí ó ṣe ma ń fi àwọn bèbí ìṣeré ọmọdé ṣeré, tí ó sì ma ń ṣe bí ẹni wípé òun ń ṣe ìtọ́jú wọn..
wikipedia
yo
Ni arin odun 1974 si odun 1982, o gba ami-eye akoko re ni Yunifasiti ilu Ife ati ami-eye Master degree re ni College of Medicine ti Yunifasiti ilu Eko, o si tun tesiwaju lati gba ami-eye Doctorate re ni Yunifasiti ilu Wales larin odun 1992 si 1997.Ise rea yan OgunShola lati se Adilémú ipo adari Yunifasiti ipinle Eko fun igba di e ni odun 2020 nigba ti wahala bẹ sile ni ile-iwe naa nitori pe awon Alaga ile-iwe naa yo adari re..
wikipedia
yo
Ó tún wà lára àwọn igbákejì adarí ilé-ìwé náà, kí ó tó di pé ó di Àlémú ipò adarí rẹ̀...
wikipedia
yo
Kí ó tó dé ipò ọ̀kan lára àwọn igbákejì adarí ilé-ìwé náà, òun ní provosti ilé-ìwé ìmọ̀ Òyìnbó(College of Medicine)..
wikipedia
yo
Àwọn ìwádí rẹ̀ wà lórí bí a ti ún kojú àwọn ààrùn tí Vgún fà..
wikipedia
yo
Oun ni oludari awadi ajo AIDS Prevention Initiative in Nigeria(Apina) ni Yunifásítì ìlú Èkó, òun tún ni alága Àjọ Infection Control Committee ti Teaching Hospital Ipinle Eko(LU)..
wikipedia
yo
OgunShola tun je Alaga National Association of Colleges of Medicine in Nigeria.Ni odun 2018, o soro lori ero re nipa kíkojú ààrùn ni Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó ní àìní ìmọ́tótó àti ìlò ogun Antibiotics ju botiyẹ lọ wà lára ìdí tí ogun apá ààrùn ò fi ká àwọn kòkòrò tó ún fa ààrùn mọ́..
wikipedia
yo
Àjọ West African Examinations Council (WAEC) jẹ́ ìgbìmọ̀ àjò Adánwò tí a dá sílẹ̀ lábé òfin ní ìwò-oòrùn Áyé láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ń lo ede Gẹ̀ẹ́sì gẹ́gẹ́ bí bí èdè ìkómọ̀, pẹ̀lú ìwé-ẹ̀ to ẹni pẹ̀lú àwọn ìwé-ẹ̀ àwọn orílẹ̀ àwọn orílẹ̀ LÁGBÀÁYÉ 91..
wikipedia
yo
Wọ́n dá ìgbìmọ̀ adánwò yìí sílẹ̀ lọ́dún 1952, láti àkókò náà, ipa tí ìgbìmọ̀ àjọ yìí ti kó nínú ètò ẹ̀kọ́ ní àwọn orílẹ̀-èdè Áfíríkà Ayìnyìn-sọ́rọ̀ bíi,Ghana, Nigeria, Sierra Leone, Liberia, àti The Gábíàbíà, kò kéré rárá, pàápàá jù lọ, àwọn ètò ìdánwò àti ìwé-ẹ̀rí tí wọ́n ti fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti àwọn aṣedánwò..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà wọ́n ṣètò ìkówójọ láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó bá kù díè káàtó fún ní Áfíríkà..
wikipedia
yo
Ọ̀gá àgbà kan ni àjọ yìí, ọ̀mọ̀wé Adéyegbé, ṣàlàyé nígbà kan pé “Àjọ náà ti ṣe ìgbénde àwọn akọ́ṣẹ́mọsẹ́ elétò Èkó, tí wọ́n ní ìtara láti ṣètò ìdánwò tó gbámúṣé, tí ó sin wúlò fun ìdàgbàsókè àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà nínú ìgbìmọ̀ àjọ yìí”
wikipedia
yo
Láàárín ọdún kan, ó máa ń tó mílíọ̀nù mẹta àwọn eniyan tí wọ́n máa ń forúkọ sílẹ̀ láti ṣe ìdánwò yìí..
wikipedia
yo
Bákan náà, àjọ yìí máa ń ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àjọ ìdánwò mìíràn, yálà lórílẹ̀ wa Nigeria tàbí àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
wà lára nkan ìwọ̀n tí wọ́n fi un wọn gigun nkan, aami rẹ ni buìlọ̀kulọ̀
wikipedia
yo
Láti ìgbà tí àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé ti fi ohùn ṣọ̀kan lórí àwọn nkan ìwọn ní ọdún 1959, ìwọ̀n ẹsẹ̀ àtàtà ti jẹ́ dédé mita 0.30..2..
wikipedia
yo
Ní ìwọ̀n àwọn Amẹ́ríkà àti Britain, ìwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà kan jẹ́ dédé ín(inch) méjìlá, ó sì tún jẹ́ ìdásí-mẹ́ta Yardi kan.
wikipedia
yo
Ní ayé àtijọ́, ìwọ̀n bàtà ẹsẹ̀ wà lára àwọn ohun ìwọ̀n ní orílẹ̀-èdè wolii, Romu, China, Fránsì ati àwọn orílẹ̀-èdè EngLisi..
wikipedia
yo
Ṣugbọn gígùn ìwọ̀n yí yàtọ̀ láti orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè ati láti ìlú sí ìlú.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Edwin Edem opóe (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkàn Oṣù Kẹwàá ọdún 1970) jẹ́ akọnimọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-obìnrin Rivers Angels..
wikipedia
yo
Wọ́n bi i ní ìpínlẹ̀ Cross River, Màmá gba iwe-ẹri akọnimọọgba lati Ile-ẹkọ ere-idaraya kan ni Ipinle Eko..
wikipedia
yo
Egbe agba-obinrin Rivers Angels ti a koko mo nigba kan ni Larry Angels F.C.) je iko egbe agbaboolu-obinrin Nigeria ti o fìkàlẹ̀ si ilu Port Harcourt, ni IpinleRivers Rivers..
wikipedia
yo
Wọ́n n gba bọ́ọ̀lù-díje ní liigi agbabuta ìdíje ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù-díje obìnrin abala àkọ́kọ́ ti Nigeria.Ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹgbẹ́ náà ọmọba Lawrence Ezeh tí ó jẹ́ ọmọ bíbí mbaise ní Ìpínlẹ̀ Imo ní ó dá ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-obìnrin yìí sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Larry Angels lọ́dún 1986..
wikipedia
yo
Lọ́dún 1991, Ìjọba Ìpínlẹ̀ Rivers gbàkóso Ikọ́ egbe Agba-obinrin naa nipa akitiyan ìyàwó gomina ìgbà náà, Arabinrin Abbe..
wikipedia
yo
Wọ́n pegedé nínú ìdíje àwọn obìnrin nígbà tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ ìdíje bọ́ọ̀lù àwọn obìnrin nínú àwọn ìdíje National Sports Festival lọ́dún 1989 ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Bakan naa won gba Ife-eye idije Ife akoko ti oba, Olu of Warri da sile ni Warri, ni Ipinle Delta..
wikipedia
yo
Chioma àjunwa ti o jẹ balogun iko ẹgbẹ agbabọọlu-obinrin ti wọn gba Ife-Eye Agbaye ti Olympic lodun Balogun iko naa lati ọdun 1988 si 1990.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mawlid, Mawlid An-NA Ash-Shaf tàbí Eid milamilad Un NANA ( LMV H&sig ni Èdè Arabic) jẹ́ ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Boke Andu, , wọ́n sì ma n sábà ṣe ayẹyẹ yí ní inú oṣù RÁ' Al-Adúnwá, tí ó jẹ́ oṣù kẹta tí ònkà osù ojú orun orun mùsùlùmí..
wikipedia
yo
Rábì' Al-àwwal Kejìlá ní ọjọ́ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọjọ́gbọ́ súnni fi ọwọ́ sí, Rábì' Al-àwwa kẹtàdínlọ́gbọ̀n sì ni ìjọ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀jọ̀gbọ́n Shia fi ọwọ́ sí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé kì í ṣe gbogbo ọ̀jọ̀gbọ́n Shia ni ó fọwọ́ sí ijo yí..
wikipedia
yo
Àwọn kan tún ma ún pé ayẹyẹ yí ní Maouloud ní ìwọ̀ oòrùn Africa.Ìtàn nípa ayẹyẹ ná ti wá láti ayé àtijọ́ nígbà tí orin àti ewì tí àwọn tàbí’un kọ láti yìn Muhammadu di ohun tí wọ́n ń kọ sí àwọn ènìyàn ..
wikipedia
yo
Ó wà nínú ìtàn pé olùdarí Musulumi àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ibi Muhammadu ní MuafafFar Al-din Gokbori (d..
wikipedia
yo
Awọn Ottomans kede rẹ ni ojo isinmi ni ọdun 1588..
wikipedia
yo
Tí a mọ̀ sí Mevd Kanarest.MaWlid jẹ́ ọ̀rọ̀ tí wọ́n ún lò ní àwọn ibi kan ní àgbáyé, bí àpẹẹrẹ, orílẹ̀ èdè Egypti gẹ́gẹ́ bí orúkọ fún ọjọ́ ìbí àwọn ènìyàn pàtàkì nínú ìtàn bí Súfì Saints.Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹgbẹ́ Musulumi ni wọ́n fi ọwọ́ sí ṣíṣe ayẹyẹ ọjọ́ ibi Muhammadu..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n, láti ìgbà tí wahhabism-safism, Debandism, Ahl-i Hadith àti Ahmadi tó dé, ọ̀pọ̀lọpọ̀ mùsùlùmí bẹ̀rẹ̀ sí un lòdì sí ṣíṣe ayẹyẹ náà, wọ́n ní kí un ṣe ayẹyẹ tó To(Pigbàgede'Ah or biìdájọ́)..
wikipedia
yo
Wọ́n Kawlid sí ọjọ́ ìsinmi ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀ èdè tí Mùsùlùmí ti pọ̀ ju ẹ̀sìn mìíràn lọ, yàtọ̀ sí orílẹ̀-èdè bí Saudi Arabia àti Qatar..
wikipedia
yo
Àwọn orílẹ̀-èdè míràn tí kì ún ṣe Musulumi ní ó pọ̀jù níbẹ̀ ṣùgbọ́n tí Musulumi pọ̀ níbẹ̀, orílẹ̀-èdè bí India, Tanzania àti Ethiópíà, àti bẹẹbẹ lọ, tún ká ọjọ́ iṣẹ́ ayẹyẹ Mawd gẹ́gẹ́ bi ọjọ́ ìtọ́jú.Orísun ọ̀rọ̀ náàwọn yọ "Mad" láti ọ̀rọ̀ Arab " tí ó dánà sí "bíbí ọmọ tàbí gbá"
wikipedia
yo
Lọwọlọwọ, wọn n lọ Mawlid lati ṣe apejuwe ibi Muhammad.Yato si pe won un lo fun ibi Muhammadu, a tun fi un se apejuwe "Awon oro ti a ko ti a si un ka tabi fi korin ni ibi isayeye ojo ibi Muhammad"ojo ibi naagege bi opolopo Musulumi tii ati awon Musulumi Shi'a se so, a bi Muhammadu ni ijo kejila Rabi' Al-Tho-arun.Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Musulumi Pupù Shia miran si so wipe ojo ketadinkógun ti Rabi' Al-Thowa ni a bi..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀rọ̀ Olóyànjiyàn ìvìwádìíf nítorí àwọn ọ̀jọ̀jọ̀ Shí Schówò bí Muhammad Ibn Y' - al-lay, Ibn Babaway, àti Zan Al- Al Al-me al ò'v tó làyàn pé òlà ibi rẹ̀ ní ojo kejìlá Rábì Al-awa ò-awa.. al- lati bí pẹ̀lú pẹ̀lú ọdún ní gbà sí sí òṣẹ òṣẹ sí ìdá ìlú ní pẹ̀lú ọdún Nàìjíríà sí ọdún ní ọdún Ọ̀do ní pẹ̀lú pẹ̀lú olú t' ] ó maa ọ̀rìẹ̀ ní ó jẹ́ tí ó * ní ọdún òrìv' ìdá gi' ] ọdún Shí ní ọdún òṣẹ tí ó * yẹ-ẹ̀ ní ọdún pẹ̀lú pẹ̀lú òṣẹ rẹ̀ tí ó jẹ́ ọmọ ìlú ' àti oníẹ̀yàn ' ní ọdún náà ọdún ọdún rẹ̀ sí ìlú pẹ̀lú òlò * pẹ̀lú al ' ní ó jẹ́ ti ọ̀té ọ̀kọ̀ ní ọdún Ọ̀kọ̀ ní ọdún náà sí pẹ̀lú ọdún rẹ̀ West ní pẹ̀lú òkọ̀ mọ́ ní òṣẹ ní Zav ori ò tún maa yẹ pa pẹ̀lú ìdá ní ọdún ò ní ọdún Ọ̀ru' ní ọdún [ẹ̀ kan gi' ní pẹ̀lú pẹ̀lú òkọ̀ * ní ọdún ò yẹ ( àwọn tí àwọn ọmọ ní ọdún rẹ̀ gi' ] tí ọdún rẹ̀ ní pẹ̀lú ò ò yẹ al bẹ̀rẹ̀ al-ẹ̀ka ' tí pẹ̀lú è yẹ ibi rẹ̀ ní ọdún rẹ̀ ] al * * rẹ̀ * ** **
wikipedia
yo
Àwọn miran tilẹ̀ sọ wípé ọjọ́ ìbí rẹ kò jẹ́ mímọ́, wọn kò sì kó sínú ìwé ìtàn Mùsùlùmí..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ nípa àríyànjiyàn ojo Mawlid ní Ibn Khallikan kọ pé ó jẹ́ àríyànjiyàn àkọ́kọ́ nípa ayẹyẹ náà.Ìtàn bí àbá ti túnkú Kaptein tí Leiden University fi lédè, àwọn Fatimi ni ó bẹ̀rẹ̀ Máw..
wikipedia
yo
Àbá pé iṣẹ́ ayẹyẹ Mawlid bẹ̀rẹ̀ ní ìdílé Fatimid ti jẹ́ àbá tí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Islam àti ìmọ̀ àwùjọ ti gbà kãkiri àgbáyé..
wikipedia
yo
AnneMarie Ísírẹ́lìcha tún sọ pé ṣíṣe ayẹyẹ ibi wòlĩ Moìkáwọ́ bẹ̀rẹ̀ láti Egypti nígbà àwọn Fatimids..
wikipedia
yo
1442) So rọ nipa okan ninu awon ayeye naa ti won se ni odun 1122, o ni opolopo ojogbon kopa ninu ayeye naa..
wikipedia
yo
Wọ́n gbọ́ ìwãsù, wọ́n pín àwọn ohun adùn, pápá jùlọ oyin, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tálákà ni wọ́n sì fún ní nkan..
wikipedia
yo
Sugbon gege bi Encyclopædia Britannica se fi lede, MuafafFar Al-din Gokbu ti Sunnis ni o bere ayeye mawlid ni odun 1207..
wikipedia
yo
àwọn kan tún sọ pé Abu Al-abpù Al-Azafi ti ìlú Cecù ni ó bẹ̀rẹ̀ ayẹyẹ Máwlid gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà láti so àwọn mùsùlùmí pọ̀ àti láti ṣe bí àwọn ayẹyẹ KTisTI8.Èrò àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n mùsùlùmí nípa ayẹyẹ náàIbn Al-Hajj sọ ṣeré nípa ṣíṣe ayẹyẹ náà gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ìdúpẹ́, ṣùgbọ́n ó lòdì sí àwọn nkan èèwọ̀ tí òun ṣẹlẹ̀ níbẹ̀…
wikipedia
yo
Ó lòdì sí àwọn nǹkan, bí kí àwọn olórin má kọrin pẹlu ìlú..
wikipedia
yo
O bere pe kini isorisi ti o lẹ́wà laarin ibi Mohamdu..
wikipedia
yo
Alhaji náà sọ pé “A gbọ́dọ̀ fi ṣiṣẹ́ rere àti fífi fún àwọn aláìní kún ìbọ̀wọ̀ fún oṣù náà”
wikipedia
yo
Bí ẹnikẹ́ni kò bá ní lè ṣe bẹ́ẹ̀, kí ó yàgò fún ṣíṣe ohun tí kò dá nínú ìbọ̀wọ̀ fún oṣù náà..
wikipedia
yo
O so wipe ohun ko lodi si Mawlid sugbon awon nkan èèwọ̀ ni won ma un se nigba Mawlid oun ko si lodi si di Dana ati pipe awon eniyan wa jẹun.Ní afikun, o ni awon miran ko se ayeye Mawlid nitori ibọwọ sugbon won fe gba awon fadaka ti won ti fun awon eniyan ni ayeye miiran,o si ni awon nkan ti o lewu wa ni iru iwa yi.S.’kh al-Islam, Abu I-àṣà-13 Ibn Kjar, "eni ti o je Hafiz ti o ga ju lo" so wipe sise sise mawlid le je nkan rere ati nkan buburu, pe bi eniyan ba se nkan rere nigba ti eniyan nse ti o si yàgò fun buburu, iyen mu ki ayeye mawlid je rere, bi o ba se be, iyen mu ki ayeye mawddd ni buburu..
wikipedia
yo
Ó ní wíwá wòlĩ náà jẹ́ rere, àti pé ọjọ́ náà nìkan ni ó yẹ kí wọ́n má fọ̀wọ̀ fun(kĩ ṣe gbogbo oṣù náà..
wikipedia
yo
Ó ní “Ó yẹ kí eniyan ṣe ohun tí ó ma bọ̀wọ̀ fún Ọlọrun, àwọn bi kika qurá, fi fi oúnjẹ fun ni, fi fi ohun ini fun ni ati kikọ orin ọpẹ́ ti ohun ran eniyan lọ́wọ́ lati ṣe ohun rere.” Ó ní àwọn “Ṣama ati eré lè wà lára àwọn nkan tí ó bá àwọn ìlànà ayẹyẹ náà ṣùgbọ́n nkan tí kò dá kọ dá.Àwọn ọ̀rọ̀ mawpẹ̀lúdpẹ̀lú àwọn atọ́ka sí bí àwọn ayẹyẹ ti ọjọ́ ibi ti Muhammad, ọ̀rọ̀ mawlid tún ń tọ́kasí àwọn ‘ọ̀rọ̀ pàápàá tí ó jẹ́ kíkọ nípaṣẹ̀ àtinúdá fún un àti sísọ ní ibi àjọyọ̀ Muhammad’ tàbí “Ọ̀rọ̀ tí a kà tàbí tí a kọ lórí ọjọ́ náà”
wikipedia
yo