cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ile ifowo pamo naa gba iwe-aṣẹ ifowopamo agbegbe nipasẹ Central Bank of Nigeria ni osu karun odun 2016..
wikipedia
yo
Abdullahi Sule (a bi ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n, Oṣù kejìlá, Ọdún 1959) jẹ́ onílàsí àti olósèlú Nàìjíríà tí ó jẹ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ Nasarawa..
wikipedia
yo
Wọ́n yan an gẹ́gẹ́ bí gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa nínú ìdìbò gómìnà ọdún 2019 lábẹ́ ètò ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress (APC).Ìgbésí ayé rẹ̀wọ́n bi Sule ni gbekẹ, Akwanga ní Ìpínlẹ̀ Nasarawa ní ọjọ́ kerindinlogbon Oṣu kejila ọdún 1959.Ní ọdún 1968, o keko ni ile-eko Roman Catholic Mission (RMC) ti o wa ni gbe Station, ti o si pari ile-eko girama ni Zang Secondary School ni odun 1974.Ni ojo kewa osu keta odun 2019, won kede adullahihi Sule bi Gomina ipinle ipinle Nasarawa ti won dibo yan.Awon itọkasiàwọn Gomina Ipinle Nasarawa..
wikipedia
yo
Igbobi College (ilé-ẹ̀kọ́ gíga Igbobi) jẹ́ àwòlo ti ìṣètò ètò nípasẹ̀ àwọn Methodist àti àwọn ilé ìjọsìn Anglican ní ọdún 1932, ní agbègbè Yaba ní ìlú Èkó, ìpínlẹ̀ Èkó, gúúsù ìwò-oòrùn Nàíjíríà Nàíjíríà..
wikipedia
yo
O tun wa lori aaye atilẹba rẹ ati pupọ julọ awọn ile atilẹba rẹ si wa ni ipo gidi ti o wa lati le..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ilé-ìwé gíga jùlọ ní ilẹ̀ Nàìjíríà, àti pé ó ti jẹ́ ilé-ìwé ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà olókìkí ti jáde..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2001 ilé-ìwé náà ti padà sí ọ̀dọ̀ àwọn tí ó nií ní atilẹba nípasẹ̀ Bola Tinubu ti ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó.ògbóǹtarìgì àwọn akẹ́kòọ́ tó ti Igbobi jáde TasLim Olawale Eliasj..
wikipedia
yo
Mbadiwe Joséphapha BaruwaJoseph Adefarasin OsinbajoBabatunde FasholaBolaji akínyẹmíṣẹgun Awolowo Kuti Kuti MudaErnest ShoLanre TejuoshoBabatunde FoWler| Balogun GbambergaJoyce IbruOlufemi Eliasdele SosimiPaul Adejọba Admiral Akíngan adupts Aworan kekere kékeré ohun to ránfin Igbobíi College Old Boys Association(UK) College Old Boys (North America)Igbobi College 1932-2006, ICoba, by J..
wikipedia
yo
Ile-iwosan Ortho— Igbobi je ile-iwosan ni ilu Eko, Nigeria.itan ile-iwosan Ortho— ti orile-ede, Igbobi, Lagos bere awon ise bii ile-ise isọdọtun fun awon omo ogun ti o gbọgbẹ lakoko Ogun Agbaye II ni ọdun 1943, lẹhin eyi o dagbasoke si ile-iwosan labẹ awọn iṣẹ iṣoogun ti Ilu Gẹẹsi ti ìgbàyi Nigeria ti ìgbàbẹ̀rẹ̀ Nigeria ni 6 Oṣu kejila 1945..
wikipedia
yo
Ile-iwosan Royal Orthohope ni ọdun 1956 tun ṣe iranlọwọ lati tọju awọn ọmọ ogun ti o farapa ati awọn ara ilu ti ogun abẹ Naijiria ti 1967-1970..
wikipedia
yo
Ọdún 1975 ni wọ́n fi ilé-ìwòsàn náà lé ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó lọ́wọ́, lẹ́yìn náà ìjọba àpapọ̀ ní ọdún 1979.Ìtọ́jú ìlera ilé-ìwòsàn náà ní agbára òṣìṣẹ́ tí ó tó 1300..
wikipedia
yo
Ile-iwosan ti wa ni bayi pe o je ile-iwosan Ortholórúkọ ti o tobi julo ni Iwo-oorun Afirika..
wikipedia
yo
Mobolaji Bank Anthony ṣe owó fún apákan titun ti ilé-ìwòsàn ti ó wà pẹ̀lú àtúnṣe ti ilé-iṣẹ́ pàjáwìrì...
wikipedia
yo
Mukhd Shehu Idris (a bi ni ojo kerin, osu kerin odun 1974) je alabojuto ati oloselu Naijiria..
wikipedia
yo
Oun ni Gomina ti a yan ni Ipinle Zamfara ninu idibo gomina odun 2019 labẹ ẹgbẹ all Progressive Congress (APC).Awon itọkasiawon Gomina Ipinle Zamfara..
wikipedia
yo
Àdúgbò náà ní ibi ìbúgbàù òpópónà epo, ìbúgbàù òpópónà Abúlé Ẹ̀gbá ti ọdún 2006, tó wáyé ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2006..
wikipedia
yo
ní ọdún 2016, ìjọba Èkó bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ọ̀kọ̀ọ̀kan ládùúgbò láti mú kí ọkọ̀ ìrìnnà dín kù tí àràádọ́ta ọ̀kẹ́ èèyàn tó ń rìn lójú ọ̀nà rẹ jẹ́ lójoojúmọ́..
wikipedia
yo
Afara naa jẹ ipari ati fifun le ni ọdun 2017.aworan itọka si..
wikipedia
yo
Muhammad inúwa Yahaya (a bi ni ọjọ́ kẹsan, osu kẹwa ọdun 1961) jẹ alabojuto ati oloselu Naijiria..
wikipedia
yo
Òun ni Gómìnà tí a yàn ní ìpínlẹ̀ Gombe nínú ìdìbò Gómìnà ọdún 2019 lábẹ́ ẹgbẹ́ All Progressive Congress (APC). àyè kò bí Muhammad inú Yahayawa ní ọjọ́ kẹsànán Oṣù Kẹwàá ọdún 1961 ní agbègbè kákafarita, ní ìpínlẹ̀ Gombe..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Alhaji Yahaya Umaru, jẹ́ oníṣòwò.ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀Yahaya lọ sílẹ̀-ẹ̀kọ́ alákọ́bẹ̀rẹ̀ ti Central nígbà tí ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Science Secondary School tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ láìní..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìkíni nínú ìmọ̀ ìṣirò owó ní ọdún 1983 nínú ilé-ẹ̀kọ́ fáfitì ti Ahmadu Bello University, Zariaiṣẹ́ iṣẹ́ ReYahaya ti ṣiṣẹ́ ní àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba àti aládàáni ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀ Bauchi ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bauchi state Investment and Property Devel company tí ó sì jẹ́ ọ̀gá àgbà àṣẹ àṣẹ òwò nílẹ̀ iṣẹ́ náà ní ọdún 1984 sí 1985..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó tún jẹ́ adarí àgbà fún ilé-iṣẹ́ A.Y.U Civil Engineering company Ltd láàrín ọdún 1993 sí 1999..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọjọ́ kinì oṣù ìjọ̀è ọdún 2018, ó jawe olubori nínú ìdìbò abẹ́lé inú ẹgbẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú ibo tí ó tó mọkaǹsà ti o fi oníwò lọ́wọ́ lọ́gbẹ rẹ̀ tí ó ń jẹ́ Muhammed Jibrinde Barbrinde lati díje sí ìwé ní ọdún 2018..
wikipedia
yo
Wọ́n kéde Yahaya gẹ́gẹ́ bí ẹni tó jáwé olúborí nínú ìdìbò sípò gómìnà ìpínlẹ̀ Gombe náà ni ọjọ́ kẹ́sà oṣù kẹta ọdún 2019 lẹ́ni tó mókè pẹ̀lú iye ìbò tí ó tó Lájí,179 láti fi fạ alátakò rẹ̀ Sẹ́nétọ̀ Usman Apata náfàdá láti inú ẹgbẹ́ Peoples Democratic Party (PDP), tí ó ní ìbò 222,868.Bákan náà ni Yahaya tún wọlé sípò gómìnà lẹ́ẹ̀kejì ní ọdún 2022 nígbà tí ó fojú alátakò rẹ̀ gbolẹ̀ pẹ̀lú ìbò tí ó tó àìnídé,8 láti inú ẹgbẹ́ ìṣèlú Peoples Democratic Party (PDP) , ìyẹn Muhammad jíbiri Barde tí ó ní iye ìbò 233,
wikipedia
yo
Ìkéde Ijawe olubori rẹ yi ni o waye lati enu osise independent National Electoral Commission (INEC), Maimúná Waziri, ti o so wipe egbe APC bori pelu ibo ti o to 74,Ọ̀gbẹ́ni ninu idibo naa.aye rẹGomina Yahaya fe iyawo meji, o si bi omo meje ti gbogbo won n gbe ni Ipinle Gombe..
wikipedia
yo
Àkọ́bí rẹ̀ lọ́kùnrin náà ṣègbéyàwó ní ọdún 2022.Oyè ìbílẹ̀ tí wọ́n fi jẹ́ Dan Majẹ̀ẹ́ Àwamatàwalen Kaltungoe le wọgmbe State Àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Mogu1961 BirthsLiving Popdeg MuslimsÀgbàlá of Gombe StatePeople From Gombe StateAhmadu Bello University IbiduAll Progressives Congress /sáwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Arlva PLC (èyítí ó jẹ́ Forte Oil PLC tẹ́lẹ̀) jẹ́ ẹgbẹ́ agbára abí, pẹ̀lú ibi Olú rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà, pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ tí ó gbooro ní ilẹ̀ Ghana..
wikipedia
yo
O ń ṣiṣẹ́ ní pàtàkì ní apá ìsàlẹ̀ ti ilé-iṣẹ́ epo àti gáàsì ti ilẹ̀ Nàìjíríà, ṣùgbọ́n o ti pín àwọn ìṣòwò rẹ̀ sí àwọn apá kan mìíràn ti èrè ìyè agbára..
wikipedia
yo
Pínpín tí ó wà ní ṣe pàtàkì ní pínpín ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn epo; Premium Motor Spirit (pms), Dig, Epo Ọkọ̀ Òfurufú, Kero, bákannáà bí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Lugts fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ àti àwọn èrò; pín káàkiri sí ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́, ilé-iṣẹ́, ọkọ̀ òfúrufú àti àwọn Ọjà Omi Òkun.Ìtàn ní ọdún 2015 wọ́n fọwọ́sí ìwé Àdéhùn $ 83 mílíọ́nù kan pẹ̀lú Siìṣee láti ṣe ìgbésókè ohun ọ̀gbìn 414 MW, iṣẹ́ náà ni wọ́n ní yóò parí ní ọdún 2016.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
ONTV Nigeria je ikanni tẹlifisiọnu ti o wa ni Ipinle Eko, Naijiria .ONTV je ikanni igbohunsafefe olokiki ni Nigeria, ONTV je ikanni ti o kókó gba ami-èye ìkànnì igbohunsafefe ti awon ènìyàn n nwo julọ ni ipinle Eko.okiki won lati ọdun 2013, ONTV ti di ikanni igbohunsafefe ti opolopo awon ile-ise ibanipolówó oja ma un pe olokiki julọ, awon ile-ise ipolowo bi media ìtaùn..
wikipedia
yo
. ní ọjọ́ 11 June ọdún 2015, ONTV ṣe ifilọlẹ lori ikanni DSTV 257 àti Gotv channel 96, wón si tẹsiwaju ní ṣíṣe àwọn oríṣiríṣi ètò ètò DSTV ati bouquet goTV.Otun le wo Akojọ ti àwọn tẹlifisiọnu ibudo ni Nigeria Akojọ ti àwọn ikanni iroyin Akojọ ti àwọn Netiki tẹlifisiọnu nipasẹ orilẹ-ede itọkasi..
wikipedia
yo
PRI ìjàpá ati Àtíòro oooo ni igba kan ri ni ilu awon eranko, iyan mu ni ile naa, ìjàpá ọlọgbọn ewe, oku ole Arise maṣe..
wikipedia
yo
Ó jí lòwúrọ̀ ọjọ́ kan, ebí ńpa gidigidi, alákọrí ló yọjú wo ilẹ̀ ìkóúnjẹ pamọ́ sí, kórí ǹkankan níbẹ̀, òwú aláǹtakùn ló gba ibẹ̀ kan, ó jáde òṣì bẹ̀rẹ̀ sí níí ronú ohun tó le ṣe, ìjàpá rántí bí ọ̀rẹ́ rẹ̀ Àtíòro ṣe nrí oúnjẹ jẹ ti ojú rẹ̀ sì ń dán gbínrín..
wikipedia
yo
O pinnu lati lọ si ile Àtíòro nigbati o de ile atihoro o kan ilẹkun, Àtíòro daa lohun pe ta lo nkan ilẹkun, ìjàpá dáa lohun pe emi ìjàpá ộrệ rẹ ni..
wikipedia
yo
ÀTÍÒRO bẹ̀rẹ̀ sí níí í kí ọ̀rẹ́ rẹ̀ pé ìjàpá tìrókò ọkọ yánníbo, fírí nìdí òkè, a jẹ́ ju olóhùn lọ, ṣé kò sí tí a rí ọ? Ìjàpá ni òun wá kìí ni, Àtíòro ní àsìkò tí ènìyàn ma nwá kí yan kó níyì, ìjàpá ni ọ̀rọ̀ pàtàkì kan ni òun bá wá wípé bí iyán ṣe mú tọ̀ yìí Àtíòro kò mọ pé iyán mú rárá, àti ìyàwó àti ọmọ Àtíòro gbogbo wọn l'ójú wọn ńdan, kínni wọ́n njẹ? Àtíòro ni ìjàpá kò ṣe fi àṣírí han, nítorípé ẹnu rẹ̀ kìí mẹ́nu, òpùrọ ni, olooloolo sì ni pẹ̀lú, ìjàpá ni òdòdó ni gbogbo ohun tí wọ́n sọ nípa òun ṣùgbọ́n tí ó bá fi àṣírí yìí han òun kò níí sí ẹ̀wù, ẹnikẹ́ni kò níí gbó, Àtíòro mi kanlẹ̀, ó ní ó dára òun yóò fi hàn, ṣùgbọ́n kò gbọdọ̀ sọ fún ẹnikẹ́ni o, ìjàpá ṣe ìlérí wípé ẹnikẹ́ni kò ní gbó lẹ́nu òun, Àtíòro ni kó máa lọ sí ilé, kó jí wá lòwúrọ̀ kutukutu òwúrọ̀ ọjọ́ kejì.ìjàpá jí lọ sí ilé Àtíòro ní kùtùkùtù òwúrọ̀, Àtíòro ni ó ti ya ìjàpá jù, pé bí àwọn ọlọ́kọ ẹmu bá ti lọ sí oko ẹmu kí ó padà wá, ìjàpá sa pamọ́ sí ibìkan, ìgbà tó ṣe díẹ̀ ó padà kan ilẹ̀kùn Àtíòro pé àwọn ọlọ́kọ tí lọ sí oko ẹmu, Àtíòro ni _*ilé kò tíì mọ̀ bí àwọn emi kó ti ń polówó ẹ̀kọ kí àwọn wa máa*
wikipedia
yo
Ìrìn àjò náà gbà wọ́n ní ọjọ́ pupọ.Ẹ̀kọ́ inú vlọ́ àìṣègbè yìí kọ́ wa pé ká má ja olè, ká má jẹ́ aláìnílọ́rùn, òpùrọ́, ati aláìmoore..
wikipedia
yo
olójú kòkòrò kò lè ní ìgbẹ̀yìn rere nítorí ìgbẹ̀yìn rẹ̀ burú jáì.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
PRI oooooo PRI yìí dá lórí ìjàpá àti ẹ̀yẹ àdàbà gẹ́gẹ́ bí a ṣe mọ̀ pé alágàbàgebè ní ìjàpá, olé àti òwa ní pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Àdàbà ni ẹṣin kan tó máa ń gùn kiri tí ìjàpá kò sí ní ǹkankan..
wikipedia
yo
Ìjàpá ronú lọ́jọ́ kan, ó sì gbèrò bí yóò ti ṣe pa ẹṣin àdàbà..
wikipedia
yo
Ó rí pé àdàbà gbayì láàrin àwùjọ èyí tí kò dùn mọ́ ìjàpá nínú..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọjọ́ kan ìjàpá dá ọgbọ́n àlùmọ̀kọ́rọ́yí, ó pa ẹṣin àdàbà..
wikipedia
yo
Ohun tí o ṣe ni pé o gé orí ẹṣin náà o bòó mọ́lẹ̀, ó wá fi ojú ẹṣin síta kí ènìyàn lè máa rí i dáadáa..
wikipedia
yo
Eléyìí yáa lẹ́nu, kíá ó gbéra ó di ilẹ̀ ọba, nígbà tí ó dé ààfin, ó sọ fún ọba pé òun ti rí ibi tí ilẹ̀ gbé lójú..
wikipedia
yo
Eléyìí ya ọba lẹ́nu, ó sì tún bi ìjàpá léèrè bóyá ohun tí ò sọ dáa lójú..
wikipedia
yo
Ìjàpá ni ó dá òun lójú, ó sì tún fi dá Ọba lójú wípé kí Ọba yan àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ pé kí àwọn lọ wo ibi tí ilẹ̀ gbé lójú..
wikipedia
yo
Ìjàpá lọ síwájú tó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní í kọrin báyìí pé;orin ààlọ́ ìjàpá ----------------mo ti rí ibi ilé gbé lójú àgbérìn--------_*—Ilé ìjàpá ----------------_*.Ammonitì rí ibi ilé gbé lójú àgbérìn --------oṣù|Christmas—ilé báyìí ni gbogbo wọn ń dà rẹirẹi lọ sí ibi tí ilé gbé lójú..
wikipedia
yo
Bí àdàbà ṣe gbọ́ ohun tí ìjàpá ṣe yìí ni ó sáré lọ sí ibi tí ó bo orí ẹ̀sìn rẹ̀ sí tí ó sì wú kúrò níbẹ̀ lọ sí ibòmíràn kí àwọn ẹmẹ̀wà ọba tó dé ibẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí ọba, ìjòyè ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ dé ibi tí ìjàpá wí, wọn kò rí nǹkankan, ni ìjàpá bá bẹ̀rẹ̀ sí tu ilé kiri títí kórí ojú kankan, ìgbà yìí ni ọba bínú gidigidi pé ìjàpá pa irú irọ́ tí ó tó báyìí àti pé ó tún da òun láàmú láti wá wo ohun tí kò sí níbẹ̀..
wikipedia
yo
Kia ni Ọba pàṣẹ pé ki wọn ó ti ojú Ìjàpá yọ idà, ki wọn si ti ẹ̀yin kìí bọ akọ..
wikipedia
yo
Báyìí ni ìjàpá fi ìlara pa ara rẹ̀ .Ekó ààlọ̀ Òdìbò yìí kọ́ wa pé kí a má máa ṣe ìlara ọmọlàkejì, ká jẹ́ kí ohun tí a bá ní tẹ́ wa lọ́rùnàwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Flying Doctors of Nigeria jẹ́ ilé iṣẹ́ ti ó ún ṣètò fífi ambulansi gbé ènìyàn..
wikipedia
yo
Dr Ola Orekunrin ni oda kale.Àpèjúwe o ni olú ọfiisi ni Ilu Eko ati omiran ni Port Harcourt pẹlu ọkọ ofurufu 20 ati oṣiṣẹ 47, 44 ninu wọn jẹ dokita..
wikipedia
yo
wọn má ún gbé àwọn aláìsàn tí ó farapa àti àwọn aláìsàn míràn lọ sí ilé-ìwòsàn, Àjọ náà ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú aládáni àti ìjọ̀àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àgbàlá ooooo lọ́lọ́ ààlọ́ mi dá lórí ìjàpá àti ìgbín..
wikipedia
yo
ni igbà láéláé , Ìjàpá fẹ́ ọmọbìnrin kan lọ́wọ́ ìgbín ..
wikipedia
yo
Akíkanjú ni ìgbín jẹ́ nínú ìṣe oko dídá, ó sì dá oko iṣu nlá sí ọ̀nà ọjà ìlú ..
wikipedia
yo
Ọ̀lẹ kan wà ó ma ń jí iṣu náà wà ní gbogbo ìgbà ṣùgbọ́n ìgbín kò sì mọ irú ènìyàn tó ń ṣe irú iṣẹ́ bẹ́ẹ̀ ..
wikipedia
yo
Ìjàpá pàápàá ń bá ìgbín kẹ́dùn nípa iṣu náà , bẹ́ẹ̀ ni òun gangan ni ó n jí iṣu náà wá lọ.Ṣùgbọ́n fèrè tí ilẹ̀ ọjọ́ kan mọ́ .Bí ìgbín tí yó kekẹ́ke lẹ dé inú ọkọ̀ rẹ̀ .Ìjàpá ni ó bá nínú ọkọ̀ rẹ̀ ti ń jí iṣu wá..
wikipedia
yo
Inú sí bí ìgbín ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ gàn nítorípé ìjàpá tí ó ń bá kẹ́dùn gan ni ó ń jí iṣu rẹ̀ wá .Ẹnú ya ìgbín púpọ̀ pé ìjàpá ti òun fún ni ọmọ tún lè máa wú irú ìwà bẹ́ẹ̀ sí òun .Ó rántí bí ìjàpá ti máa bá òun kẹ́dùn lórí ọlẹ̀ tí ó máa jí iṣu òun wá..
wikipedia
yo
Ó sì pinnu pé òun yóò fi ìjàpá ṣe ẹlẹ́yà dé ààyè kan.Ọjọ́ ọjà ni ọjọ́ náà jẹ́, nítorí náà ,ìgbín dé ìjàpá mọ́lẹ̀ sí ojú ọ̀nà ,gbogbo àwọn èrò tí ó ń lọ ọjà sì bẹ̀rẹ̀ sí í fi ṣe ẹlẹ́yà .Wọ́n ń sọ pé ‘Hwù ! Ìwọ ìjàpá aláìní yìí ! Ẹni tí ó fún ọ lọ́mọ ni ó sì tún lọ jí ní iṣu wá..
wikipedia
yo
Sí o , ọlọ́ṣà ! Ìjàpá ìjàpá dá kẹ́ , kò wí nǹkan kan títí wọn ẹ̀rọ ọjà fi kọjá tán.Lẹ́yìn o ò sìí iré bẹ́ ìgbín .ó wá bi ìgbín pé ,gbọ́ mi ná o; ó wá tó gẹ́ẹ́ báyìí o; jọ̀wọ́ tú mi sílẹ̀ o.Lótìítọ́ mo ti ṣe ohun tí kò dára , mo sì jèrè gbogbo èébú tí àwọn èrò ọjà ti ń búmi; ṣùgbọ́n yóò burú kí wọ́n tún bá mi báyìí ní àbọ̀ ọjà o.Nítorí náà ,jọ̀wọ́ tú mi sílẹ̀ Ọlọ́run ! Ṣùgbọ́n ìgbín kò fẹ́ ìjàpá ìjàpá sílẹ̀ ;ó fẹ́ kí àwọn èrò ọjà tún bú u ní àbọ̀ ọjà .Láìpẹ́ lọ títí ,àwọn èrò ọjà bẹ̀rẹ̀ sí í padà dé o,wọ́n sì tún bá ìjàpá lórí ìdè níbi tí ó ń ṣe ojú mi pẹ́ú .Ẹnu yà wọ́n wọn púpọ̀ púpọ̀,wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í bú ìgbín báyìí Họ́wù , ìgbín , ó fẹ́ pa á ni? Ọ̀tọ̀ kì í jóná pé ó jẹ́ àna rẹ̀ rẹ̀ nìyí nìyí! Ṣé bí òun pẹ̀lú ọmọ rẹ̀ ni wọ́n jọ ń jẹ iṣu náà ! Èyí mà le o! Bí kò bá jẹ́ àna rẹ̀ ńkọ́ ńkọ́, pípa ni ó bá pa á , ojú ti ìgbín púpọ̀, nígbà tí gbogbo wọn ń bú ìgbín ní ọ̀rẹ́ gbá gbá báyìí , ó sì tú ìjàpá sí ilé..
wikipedia
yo
Nígbà náà ni ìjàpá wá bẹ̀rẹ̀ sì í fi ìgbín ṣe ẹlẹ́yà.Ó ní ,'kò tán ní ìdí rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìwọ́ ìgbín ! O bá ti tú mi sílẹ̀ nígbà tí mo ti bẹ̀ ọ́ , ìba yé ọ títí ..
wikipedia
yo
Àṣejù rẹ ni ó jẹ́ kí o tẹ́ yìí .Èyí ni àwọn àgbàlagbà ṣe máa ń pa á lówe pé ,‘ẹ̀ àlòẹ́ ni ti ahun , t'abo ní ti àna rẹ̀ ;ẹ̀kọ inú ààìwà kò àṣejù kò dára o.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ile-iwe Greensprings jẹ ile-iwe British kan ni Nigeria..
wikipedia
yo
Ile-iwe naa ni aye fun awọn ọmọ CALLY, ṣọ̀fọ̀, alakọbẹrẹ ati sekondiri..
wikipedia
yo
Ile-iwe naa ni ogba mẹta, ogba Anthony, Lekki-Eti-Osa ati Ikoyi.Itan ile-iwe naa bẹrẹ bi ile-iwe Montessori ni Oṣu Kini ọdun 1985, pẹlu awọn ọmọ ile-iwe mẹta (3), ni aarin ilu Eko..
wikipedia
yo
Lagos State Task Force Against Human Trafficking (Ẹgbẹ́ Agbófinró ti Ìpínlẹ̀ Èkó tí ó lòdì sí gbígbé káàkiri èèyàn fún iṣẹ́ ibi tàbí láti tà wọ́n dànù) jẹ́ ẹgbẹ́ iṣẹ́-ṣíṣe ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ṣètò láti dojú kọ gbígbé káàkiri ènìyàn nípasẹ̀ ìlànà ìbí àti ìrìnàjò láti kúrò ní ìlú ní ọ̀nà tí ó báṣ..
wikipedia
yo
Gomina alaṣẹ ti ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu ṣe ifilọlẹ Ayan Ẹgbẹ-iṣẹ ti Ipinle lori gbigbe kaakiri eniyan ni ile ijọba ni ojo kejo Oṣu Kẹsan, ọdun 2020, pẹlu ipinnu gbogbogbo ti ṣiṣakoso idahun ti ọpọlọpọ awọn apa kan si idena ti gbigbe kaakiri eniyan, funni ni iwọle si Idajo fun awọn olufaragba ti gbigbe kaakiri, ibaniròjò ti awọn pàdánùja fun ẹtọ ati imudara ilana ti ìmúpadàbọ̀sípò aṣeyọri ti awọn iyoku si ipo ti ara, Imọ-ọrọ Awujọ, Iṣẹ-ṣiṣe ati Alaafia eto-ọrọ..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ iṣẹ́ yìí tí ń ṣe àtúnṣe ní àwọn ìpínlẹ̀ ìhà ìwọ̀ oòrùn gúúsù míràn ní ilẹ̀ Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Nigeria Civil Aviation Authority ( NCAA ) ni alase fún àwọn ọkọ òfúrufú ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .Adarí agbá ilé-iṣẹ́ náà ni Capt..
wikipedia
yo
Musa Shuaibu Nuhu ↑damoinSIurd.Awon Oroko olu ile-ise (Olu gbogbo ile-iṣẹ) won wa ni papa papa ọkọ ofurufu International Nnamdi Azikiwe ni olu-ilu Naijiria-ede Naijiria, Abuja ..
wikipedia
yo
O ni awọn ọfiisi agbegbe ni papa ọkọ ofurufu International Murtala Muhammed ni Ikeja Ipinle Eko, ti o tun n ṣiṣẹ bi olu ile-iṣẹ ti ile-iṣẹ naa, papa ọkọ ofurufu International Port Harcourt ni Port Harcourt, ati ni Kano .Awọn itọkasi ijọba ile Naijiria..
wikipedia
yo
Àgbàlá oooo itan mi dá lórí ìjàpá ọlọgbọn Ewe ati Ògbójú ọdẹ..
wikipedia
yo
ọkùnrin kan wà láyé àtijọ́, Ògbójú-ọdẹ ni, ṣùgbọ́n bi ó ti pa ẹran tó, kò fi dá nkan ṣe..
wikipedia
yo
ọ̀pọ̀ ìgbà, ki ri ẹran ti ó bá pa tà, o ma ńpin fún ará ilú ni..
wikipedia
yo
Nigbati ko ri ẹran pa mọ́, o di Ọdẹ-apẹyẹ.Ni ọjọ́ kan, Ògbójú-ọdẹ yi ri ẹyẹ Òfú kan, ṣùgbọ́n ọta ibọn kan ṣoṣo ló kú ninú ibọn rẹ..
wikipedia
yo
gẹ́gẹ́bí Ògbójú-ọdẹ, ó yin ẹyẹ Òfú ni ibọn, ọta kan ṣoṣo yi si báa..
wikipedia
yo
Ó bá wọ igbó lọ láti gbé ẹyẹ tí ó pa, láì mọ̀ pé ẹyẹ yí kò kú..
wikipedia
yo
ó ṣe akitiyan lati ri ẹyẹ́ yi mu, kẹ̀rẹ̀kẹ̀rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ si wọ igbó lọ titi ó fi si ọ̀nà dé ilẹ̀ àwọn ará ọrùn àwọn ti wọn ńpè ni Abà-ẹ̀dá..
wikipedia
yo
inú bí àwọn ará ọ̀run nítorí Ògbójú-ọdẹ yi jálu ipàdé wọn..
wikipedia
yo
wọn gbámú, wọ́n ní kí ó ṣe àlàyé bí ó ṣe dé ilẹ̀ wọn kí àwọn tó pa..
wikipedia
yo
ọdẹ ṣe àlàyé ohun ti ojú rẹ ti ri nipa iṣẹ́ àti jẹ àti gbogbo ohun ti ojú rẹ ti ri lẹ́nu iṣẹ́ ọdẹ..
wikipedia
yo
àwọn Ará-Ọ̀run ṣe àánú rẹ, wọn bèrè pé ṣe ó lè dá ẹmu, ó ni ohun lè dá ẹmu diẹ-diẹ..
wikipedia
yo
Wọ́n gbàá ní ìyànjú pé kí ó máṣe fi ojú di iṣẹ́ kankan, nítorí náà, kí ó bẹ̀rẹ̀ sí dá ẹmu fún àwọn.Wọ́n ṣe ìkìlọ̀ pé, bí ó bá ti gbé ẹmu wá, kò gbọdọ̀ wo bi àwọn ti ńmu ẹmu, ki ó kàn gbé ẹmu silẹ ki ó si yi padà lai wo ẹ̀hin..
wikipedia
yo
Bi ó bá gbé ẹmu dé, á bẹ̀rẹ̀ si kọrin lati jẹ́ ki àwọn ará orun mọ̀ pé ohun ti dé, lẹhin eyi á gbé ẹmu silẹ á yi padà lai wo ẹ̀hin gẹ́gẹ́ bi ikilọ Ará Ọ̀run..
wikipedia
yo
Ni ọjọ́ keji, a bá owó ni idi agbè ti ó fi gbé ẹmu tàná wá..
wikipedia
yo
Ìjàpá ọlọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́ sọ ara rẹ̀ di ọrẹ kòrí kòsùn pẹ̀lú Ògbójú-ọdẹ nitori àti mọ idi ọrọ̀ rẹ..
wikipedia
yo
láìpẹ́, àrùn Ṣọ̀pọ̀ná bo Ògbójú-ọdẹ eleyi dá iṣẹ́ àti gbé ẹmu fún àwọn Ará Ọ̀run dúró..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi ọrẹ o bẹ Ìjàpá pe ki ó bá ohun bẹrẹ si gbé ẹmu lọ fún àwọn Ará Ọ̀run..
wikipedia
yo
ó ṣe ikilọ fún Ìjàpá bi ikilọ ti àwọn Ará Ọ̀run fi sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ìjàpá, bẹ̀rẹ̀ si gbé ẹmu lọ, ni ọjọ́ keji ti ó ri owó rẹpẹtẹ ti àwọn Ará Ọ̀run kó si idi agbè ẹmu àná, ó pinu lati mọ idi abájọ..
wikipedia
yo
Ìjàpá fi ara pamọ́ sí igbó láti wo bí àwọn ara ọ̀run ti ńmu ẹmu..
wikipedia
yo
Ohun ti ó ri yàá lẹ́nu, ó ri Ori, Ẹsẹ̀, Ojú, Apá àti àwọn ẹ̀yà ara miran ti wọn dá dúró, ti wọn si bẹ̀rẹ̀ si mu ẹmu..
wikipedia
yo
Nigbati wọn gbọ, wọn le lati pa ṣùgbọ́n, Ìjàpá sá àsálà fún ẹmi rẹ, ó kó wọ inú ihò, wọn kò ri pa.Ògbójú-ọdẹ reti titi ki Ìjàpá kó owó ẹmu dé..
wikipedia
yo
nígbàtí Ìjàpá dé, ó gbé irọ́ kalẹ̀ pé olè dá ohun lọ́nà, wọn gba gbogbo owó ẹmu lọ ni ohun ṣe pé.Ara Ògbójú-ọdẹ ya, ó gbé ẹmu lọ fún Ara-Ọ̀run gẹgẹbi iṣẹ́ rẹ tẹ́lẹ̀ lai mọ iwà àkóbá ti Ìjàpá ti hù silẹ.Àwọn Ará-Ọ̀run wọ ijàkàdi pẹ̀lú Ògbójú-ọdẹ, nitori ó rú òfin ikilọ ti wọn fun..
wikipedia
yo
nítorí ìmọ̀ tí ó ni lẹ́nu iṣẹ́ ọdẹ, Ará-Ọ̀run kò ri Ògbójú-ọdẹ pa..
wikipedia
yo