cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
O ti sise lori opolopo awon ere iriri ati awon ere àròṣe, o si ti ko iwe-itan kan ti akole re je the Imru Peace Maker.àṣàyàn awon ere re broken Dreams (2011) The Lodby (2015) a Stray (2016)àwọn itọkasiàwọn ìtàkùn ìjásóde awon eniyan alààyè.. | wikipedia | yo |
Rehema ko ipa suẹ̀jẹ́ ninu ere Yya Jèhófàdt ni ọdun 2016, ìyẹn sí ló jẹ́ kí ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tó dára jù lọ ní Uganda Film Festival ní ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
Nanfuka ṣe adarí fún eré Verónica wish, ó sì gba àmì ẹ̀yẹ adarí eré tó dára jù lọ láti ọ̀dọ Uganda Film Festival ní ọdún 2018, òun sì ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó ma gba àmì ẹ̀yẹ náà.. | wikipedia | yo |
Ó kó ipa Lady Macbeth nínu eré orí ìtàgé ti Macbeth.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, ó wà lára àwọn tí ó fi ohun ṣe ère fún The Cow needs a wife.. | wikipedia | yo |
O gbe igba ọ̀rọ̀ke nibi idije Kampala Sale ni ọdun 2013.. | wikipedia | yo |
O jẹ AmBasedo fun ile ise Airtel Uganda, Airtel Malawi, milkman Uganda ati wíwà Bank Uganda.Àwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Malaika Tenshi Nyánzi ti oruko inagi re je Malaika je osere, modeli ati agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórílẹ̀ ede Uganda.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bi atọ́kùn fún ètò D'Mighty Breakfast lóri KFM àti ètò Malaika àti oúlanya lórí Capital FM.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínú eré Verónica's wish, bed of thorns, the Honhonobles and Mela.Iṣẹ́ Malaika bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ modeli ní ìlú Nairobi lórílẹ̀ èdè Kẹ́ńyà kí ó tó wá padà sí Uganda.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn tí ó padà sí Uganda, ó darapọ̀ mọ́ Urban Television, òun àti Gaẹtanó sì jẹ́ atọ́kùn fún ètò Urban today.. | wikipedia | yo |
O darapọ mọ Rockstar Group, o si jẹ atọkun fun eto Shoooosh! Malaika bẹrẹ ere ṣiṣe pẹlu ere Verónica's wish.. | wikipedia | yo |
O ko ipa Stella ninu ere Bed of thorns, eyi si lo je ki won fun ni ami eye osere binrin to dara ju lo lati odo Uganda Film Festival.igbesi aye re o gboye ninu imo International Business lati ile eko giga ti United State International University Africa ti o wa ni Nairobi.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2018, ninu 'ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nu'ro ti Crystal Newman ṣe fun, o sọ wi pe oun ni arun wárápá.Awon Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Kantorí KubirYaba Anne (Bii ní ojo ketala osu kerin odun 1986) ti o gbajumọ gege bi Anne Kanjìnná je osere ati alawada lorilẹ ede Uganda.Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹpẹ Aye ati eko re won bi Anne si ilu Mparo ni agbegbe Kabalẹ District.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ kòbalẹ Primary School àti Bwé Girls' Secondary Secondary School kí ó tó tẹ̀síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Makere University níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ Social Science.Iṣẹ́ Anne bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe eré láti ọdún 2007 pẹ̀lú ẹgbẹ́ Theatre Factory.. | wikipedia | yo |
Òun ni olùgbé kalẹ̀ ètò Don't Mess with Kanẹ̀fọ́ tí ó jẹ́ ètò ìtara.Àṣàyàn eré rẹ̀ ẹ̀yẹ ẹ̀yẹ Honorary Recognition láti ọ̀dọ síike Rising Star Academy Awards, gẹ́gẹ́bí "Queen of Comedy" 2018 Comedy YouTube Sub-Saharan Africa Creator Award 2016 Outstanding Female Cocean 2016 Theguce fúnniest Cocean 2016 African Entertainment Awards USA, Best Cocean's Award 2015 Rising Star - Cocean of the Year 2015 African Oscar Award for Favorite Cocean 2015 Nollywood & African People's choice Award for Favorite Cocean 2015 YouTube Silver Play button 2015 Airtel Women Women of Subce Awards G Beffta 2013 (Best Cocean) Ríte Lagos International 2013 (Best Actress) Ríte Social Media Awards (Àgbàlá celebrity) Ríte African Social Awards Red (Ásà) - 2013 ( Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Akite Agnes (Bii ni ojo kokandinlogun osu keta odun 1983) jẹ oṣere ati alawada lorilẹ-ede Uganda.Eko rẹ Akite gboye ninu Tourism lati Ile Eko giga ti Mkere University.Iṣẹ ni ọdun 2014, Akite bẹrẹ awada sise pelu egbe The Punchliners… | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó kópa nínú eré Girl From Mpàrọ̀ gẹ́gẹ́ bí Màmá Brian.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kẹfà Ọdún 2018, ó kópa níbi ayẹyẹ Kampala Comedy Festival èyí tí òkèllo Òkèlo gbé kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Laarin osu kejo ati osu Kọkànlá, egbe ugh PineApple Comedy Tour ti o wa gbe lo orisirisi ilu bii Mbale, keji, Fort portal, Jinja ati Mbarara.. | wikipedia | yo |
O ṣe awada nibi eto apa kẹrin ti African Laughs ni ọjọ kẹjọ oṣu Kẹwàá ọdun 2018.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kẹta Ọdún 2019, ó gbé ètò Arise Woman! Comedy Jam kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní oṣù náà ni ó tún farahàn ní Kìgálì fún ayẹyẹ ṣèkà Fest.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Keje Ọdún 2019, ó wà lára àwọn tó ṣe ìtara níbi ayẹyẹ Laugh Festival ní Nairobi.Igbesi ayé rẹ̀ Akite jẹ́ ọmọ karun-un nínú ọmọ mẹ́jọ tí àwọn òbí rẹ̀ bí.. | wikipedia | yo |
Anita Kyaríṣo jẹ́ òṣèré, atọ́kùn ètò àti oníṣòwò lórílẹ̀ èdè Uganda.. | wikipedia | yo |
Ní oṣù keji ọdún 2019, ilé iṣẹ́ Goodwill Tourism fi ṣe AmBase wọn.. | wikipedia | yo |
Kí ó tó ṣe atọ́kùn fún ètò Be my date lórí NTV ní ọdún 2014, ó ti jẹ́ ipò Omidan Uganda ti apá ìwọ̀ ọrùn.. | wikipedia | yo |
O ti ṣe atọkun fun awọn ayẹyẹ bii Africa Magic ríránr's choice awards ni Nigeria (2016), Namibia Annual Music Awards (2016 ati 2017), Ghana Movie Awards 2017, Ghana Music Awards 2016, ati Glitz Awards Ghana 2017.Iṣẹ Anita bẹrẹ iṣẹ Rch nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mejila, ó sì ṣiṣẹ́ pẹ̀lú flair Gbasin ní ọdún 2008.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2013, o kopa ninu ìdíje Omidan Uganda, o si gbe ipo keji.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí Oriwewe ní ọdún 2014 pẹ̀lú ètò Be My date.. | wikipedia | yo |
Faọlábi gbajúmọ̀ fún ipa gbòngbò tí ó kó nínú eré Second Chance ní ọdún 2016.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2018, ó di ọmọ orílẹ̀ ède Uganda àkọ́kọ́ tí wọ́n ma pè sibi ayẹyẹ Cannes Film Festival.. | wikipedia | yo |
Ni osu keji odun 2019, won fi se ambase fun Tulam .. | wikipedia | yo |
O tun jẹ Ambako fun Cat footwear, Paramour Cosmetics, lux Belaire, Virginia Black MTN Pulse, Jumia Uganda ati Olau Uganda.Bíọlábi da egbe Fáb Girls Foundation kale lati le ma pese iranlọwọ fun awọn obinrin.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Barlen Pyamootoo (tí wọ́n bí ní 27 Oṣù Kẹẹ̀sán Ọdún 1960) jẹ́ olùgbéré-jáde olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Mauritius.. | wikipedia | yo |
Étienne "%ga (22 Oṣù Kínní Ọdún 1942-17 Oṣù Kẹẹ̀ta Ọdún 1997) jẹ́ ònkọ̀wé àti ònkọ̀tàn eré ọmọ orílẹ̀-èdè Olómìnira arin Afrika.. | wikipedia | yo |
Wọ́n jẹ́ àwọn ìran Angola tí ó yẹ níbi jàm̀bá ọkọ̀ ojú-omi kan tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 1540.. | wikipedia | yo |
fíìmù náà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn fíìmú tí wọ́n gbéṣẹ́ gbogbo ẹ̀tọ́ rẹ lórílẹ̀-èdè São Tomé and Príncipe.Àwọn olùkópa Nezo as himself - painter, musician, Stoptortor ṣàkọsílẹ̀ Sr.. | wikipedia | yo |
As himself - rẹ̀Tired Fisherman Baltazar Squarekì as himself - student Julieta Paulina Lunda as himself himself -man bíbí, da Silva as himself - Fisher who no longer fishes Fernando Sr.. | wikipedia | yo |
As himself - merchant Antônio soares PEREIRA as himself - Fisherman Liga Liga as himself - heAle dance group of s.. | wikipedia | yo |
João dos Angolares as themselves Voice of the King Group as themselves Bulaue Group as themselves Congo Dance Group as themselves Anguene Group as themselvesáwọn ìtọ́kasíàwọn Ìtàkùn Ìjásóde Mionga kí ọ̀bọ in YouTube.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà dá lóri òṣìṣẹ́ tẹlifíṣọ̀nù tẹ́lẹ̀ rí tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Paula Williams Madison àti àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ okùnrin méjì kan tí wọ́n rin ìrìn-àjò láti lọ ṣe ìwádìí nípa bàbá ìyá wọn tí ó fi ìyá wọn sílẹ̀ sí Jàmáíkà ní àsìkò àwọn ọdún 1930.Fíìmù náà gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àmì-ẹ̀yẹ níbi àwọn ayẹyẹ àjọ̀dún fíìmù.. | wikipedia | yo |
Àfihàn àkókò fíìmù náà lórílẹ̀-èdè Jàmáíkà wáyé lórí ìkànnì Doc World ní ọjọ́ 14 Oṣù Kaàrún, Ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
O sìí tun wa lori ayelujara fun awọn eniyan lati wó lọ́fẹ̀ẹ́ lati 15 Oṣu Kaàrún titi di 13 Oṣu Kẹfa ọdun 2017.. | wikipedia | yo |
Wọ́n wo fíìmù náà níbi ayẹyẹ Pan African Film Festival ní Ọjọ́ Kẹẹ̀jọ Oṣù Kejì, ọdún 2014.Àwọn olùkópa Paula Williams Madison ElRick Williams Howard Williams Vincent J.. | wikipedia | yo |
Figègé CID (tí wọ́n bí ní 18 Oṣù Kínní, Ọdún 1957), jẹ́ òṣèrékùnrin, olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Portugal.Ó ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù ilẹ̀ Yú àti ilẹ̀ Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Steos Pavlakis (tí wọ́n bí ní ọdún 1974) jẹ́ olùdarí eré, ònkọ̀tàn àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Gíríìsì.. | wikipedia | yo |
O ti lọ́wọ́sí tó sì ti nípa lọ́lọ́lọ́pọ̀ nínú àwọn sinimá orílẹ̀-èdè Benin pẹ̀lú ṣíṣe àwọn fíìmù ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ bíi The Eye of the Beholder, Studio Har àti Drive Through.àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1974àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Marc Serena (tí wọ́n bí ní ọdún 1983) jẹ́ olùgbéré-jáde, olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Spain.. | wikipedia | yo |
Pablo César (tí wọ́n bí ní 26 Oṣù Kínní, Ọdún 1962), jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Argẹntínà.. | wikipedia | yo |
Ó ti sísí sinimá ilé Afrika pẹ̀lú pàpà àwọn eré bíi Equinox, the garden of the Roses, Los dioses de agua àti Aphrodite, the garden of the perfumes.Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1962àwọn ará Argentináàwọn ènìyàn ALÀÀàwọn àyọkà aláìní ohun-inú Wiki—inú | wikipedia | yo |
Cecilia Zoppelletto jẹ́ olùdarí eré lóbìnrin àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Italia.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún dídarí eré ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ kan lórílẹ̀-èdè Kóngò, èyí tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ La Belle at The Movies.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ni 1967àwọn ènìyàn alààyè.. | wikipedia | yo |
Ernest Napoleon jẹ́ òṣèrékùnrin àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Rọ́síà àti Tànsáníà.àwọn Ìtọ́kasíàwọn ààwọn òǹṣèwé The Swedish Actor Ernest Napoleon a Scandinavian Talent àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Adérérẹ̀mí àlùkò’’ ti gbog ènìyàn tun mo si Igwe, baba atat , àjẹlà''' àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ jẹ́ olórin ọ̀kọrin Fújì àti òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìgbà èwe túnsún bí rẹmi Àlùkò ní ìlú Èbúté mẹ́ta ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1977.. | wikipedia | yo |
Àmọ́, àwọn bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ileṣa ní ìpínlẹ̀ Osun tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Abeokuta ní ìpínlẹ̀ Ògùn ní orile-ede Nàìjíríede | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, rẹmi ma ń tẹnu mọ́ wípé ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Èkó ni òun ń ṣe.. | wikipedia | yo |
Olórin Fújì yí jẹ́ ẹlẹ́sìn ọmọ lẹ́yìn Kírísítì, bí ó tilẹ̀.jẹ́ wípé wọ́n ma ń fọn rere rẹ̀ wípé àwọn ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí ní wọ́n lórin Fújì.ìlera-wúyẹ́ nípa ojú rẹ̀lásìkò ìgbà kan, ìròyìn gbé tẹ́tẹ́-wúyẹ́ tí ó ń jà ràn-á nípa àlùkò wípé Ofúù pàdánù ojú rẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ariane Astrid Atodji (tí wọ́n bí ní ọdún 1980) jẹ́ olùdarí eré, olùgbéré-jáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdèKamẹrúùnù.. | wikipedia | yo |
O ti se opolopo awon ere itan-akọọlẹ to fi mo kóundi et le Jeudi National ati La soufFrance est une école de sagesse.Awon itọkasiàwọn ìtàkùn ìjásóde arianeane kowe atodjiàwọn Ọjọ́ìbí ni 1980àwọn ènìyàn alààyẹ̀.. | wikipedia | yo |
Claude Haffner (tí wọ́n bí ní ọdún 1976) jẹ́ olùdarí ère àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Fránsì àti Kóńgò.. | wikipedia | yo |
O ti se opolopo awon ere itan-akọọlẹ to fi mo ko BONU Mutu, Defilé Celianthe ati Noire Ici, Blanche La-Bas.Awon itọkasi awon Ọjọ́ìbí ni 1976awon eniyan Alààyè.. | wikipedia | yo |
Mutira Ray èyíwùmí tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí múka Ray ni ó jẹ́ ọmọ bíbí gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé Ray Lewunmi tí wọ́n bí ní ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹrin ní opopona "Olùṣọ́ ní ìlú Bariga ní ìpínlẹ̀ Èkó, amo tí ó àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìrẹpòọ ní ìpínlẹ̀ Kwara jẹ́ òsèré orí-ìtàgé, àti sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.ètò Èjá-ẹ̀kọ́ rẹ́mú lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Aud, ní ÌlúÒṣogbo, ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama Gu àrán orin Comprehensive High School ní ìpínlẹ̀ Kwara, ṣaájú kí kí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Gbogbonìṣe ti Ìpínlẹ̀ Kwara.Iṣẹ́ rẹ̀.Gẹ́gẹ́ bí òṣèré ní bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe láti ìgbà èwe. tí ó. ti wà. Ní ilé-ẹ̀kọ́ girama. Baba rẹ̀. Ó jẹ́ òṣèré ní àsìkò.Ọdún 1970, tí bàbá rẹ̀ ní àwọn fún ní àádọ́ta kọ́bọ̀ nígbà náà gẹ́gẹ́ bi owó oya ipa tí ó kó nínú eré.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínú eré gẹ́gẹ́ oníránṣé fún ọba nínú eré Edie bá lókun.Àwọn Àsàyan eré rẹ̀ Abọrẹ̀, Ọbalúayé,36 kìnìún,Ìyá lálá bàáro àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Manouchka Kelly Labouba jẹ́ olùdarí eré, olùgbéré-jáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Gàbọ̀n tó maá n sábà daŕi àwọn eré oníṣókí.. | wikipedia | yo |
Ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré oníṣókí, lára wọn ni Marty et la tendre dame, Le Guichet automatique àti Le divorce.. | wikipedia | yo |
Ó tún maa ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olóòtú sinimá àti olùyàwòrán.Àwọn ìtọ́àwọn ẹlọ́è ìjáde Interview de Manouchka Kelly Kelly Labouba 1 Interview de Manouchka Kelly Labouba 2 Manouchka Kelly Labouba publication ènìyàn òkẹrin.. | wikipedia | yo |
Kalifa dienta (ti wọ́n bi ni 1 oṣu kinni, odun 1940) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Mali.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún dídarí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ A Badi.. | wikipedia | yo |
Ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi ònkọ̀tàn àti olùyàwòrán.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1940àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Hind Bensari (tí wọ́n bí ní ọdún 1987) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Mòrókò.. | wikipedia | yo |
Aïcha elhadj Macky (8 Oṣù Kínní Ọdún 1982) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nìjẹ̀r.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún dídarí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Fruitless Tree.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn Ìtàkùn ìjád Film Direlẹ́nu Ọjọ́ìbí ní 1982àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Musanase Laura (tí wọ́n bí ní ọdún 1993) jẹ́ òṣèrébìnrin lórílẹ̀-èdè Rùwándà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèrébìnrin tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Rùwándà látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré tẹlifíṣọ̀nù aláwàdà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ City Maid.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn àrùàwọn ìjásóde Some of the Well-known in Rwandan Cinéma are proud of Its Knnmentsments àwọn Ọjọ́ìbí ní 1993àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ara Rùwándà.. | wikipedia | yo |
Munlle Aline (tí wọ́n bí ní ọdún 1994) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Rùwándà.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi "Milika" nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Syca.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1994àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
MuKàkào Beatha jẹ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdèRùwáńdà.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ giramata gẹ́gẹ́ bi ìyá sí giramata.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Rayge ùsaramwezi (tí wọ́n bí ní ọdún 1993) jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Rùwándà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré tẹlifíṣọ̀nù tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Rùwándà.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi Nana nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ City Maid.. | wikipedia | yo |
Ó tún maa ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí aṣàpẹẹrẹ èè aṣọ.Àwọn ìtọ́pọ̀ àwọn ènìyàn ìkẹrinpọ̀ ní 1993àwọn ará rẹ̀ Rùwáńdà.. | wikipedia | yo |
Bahavu Uase Jeannette jẹ́ òṣèrébìnrin àti atọ́kùn ọmọ orílẹ̀-èdè Rùwándà.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi Diane nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ City Maid ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi aṣàpẹẹrẹ ẹ̀ṣọ́ aṣọ.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn ìtàkùn ìjáde Diane Wakinaga múrí City Maid Yambits impéta y'Ọ̀gáv)". Idarayágágá múrí cinema ńyaRwanda, bagi Batsindira Ibihembobo Múv "Rwanda International Movie Awards ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
O ti kopa ninu ọpọlọpọ awọn fiimu bii The Chains of Love, Dreams, SakaBaka, Rwabo, Sebukokokoko, Uruibí ati The Secret of Happiness.. | wikipedia | yo |
O tun maa n sise gege bi osise ilera.Awon itọkasiawon Ìtàkùn ìjásóde Rwanda International Movie Awards Kuri uyu wa Gatanu Abakunzi ba filime baramurikirwa iyitwa awon eniyan alààyèawon ara Rùwáńdà.. | wikipedia | yo |
PaSCale Lamche (tí wọ́n bí ní Oṣù Keèje, Ọdún 1960) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdèFránsì àti Gúúsù Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Ọlásún Ray èyíwùmí tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Lásún Ray jẹ́ ọmọ bíbí ògbóntanta òṣèré Yorùbá tí ó ti di olóògbé pa Ray èyíwùmí, ó jẹ́ òṣèré, adarí eré, àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìgbà èwe àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀wọ́n bí Súnkànmí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́ osù kíní ní Ìpínlẹ̀ Kwara.. | wikipedia | yo |
Iṣe rẹ gẹ́gẹ́ bi oṣereo bẹrẹ ere ori-itage ni ọdun 1972, amo ti o gbe ere rẹ akọkọ jade ti o pe akole rẹ ni Korde.. | wikipedia | yo |
O tun gbe ere kan ti akori re n je the Bridge' ti o mu gba ami-eye eye ti AmV’’ ni odun 2018.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Waris Dirie (bíi ní ọdún 1965) jẹ ◆ch, òṣèré àti ajìjàgbara lórílẹ̀-èdè Uganda pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí Dirie ní ọdún 1965, ó sì jẹ́ ìkan lára àwọn ọmọ méjìlá tí àwọn òbí rẹ̀ bí.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹtala, ó sá kúrò nílé nítorí àwọn ẹbí rẹ̀ ni kí ó fẹ́ arakunrin kan tí ó jẹ́ ọmọ ọgọta ọdún.. | wikipedia | yo |
Wọ́n mú lọ sí ìlú London láti lọ se ọmọ ọ̀dọ̀.Iṣẹ́ ní ọdún 1987, ó kópa nínú eré The Living Daylights èyí tí James Bond gbé kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2015, Dirie sọ̀rọ̀ nípa bí wọ́n ṣe ṣiṣẹ́ abẹ fún ohun nígbà tí ohun wà ní ọmọ ọdún márùn-ún.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1998, òun àti Cathleen Miler jọ kọ́ ìwé Desert flower.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2004, ó gba àmì ẹ̀yẹ World Social Award láti ọ̀dọ Women's World Award Gala ní ìlú Hamburg lórílẹ̀-èdè Germany.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2007, Al Jazeera pe Warris Dirie láti wá sọ̀rọ̀ lórí Female genital mutílation.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2009, wọ́n ṣe ère Desert flower lórí ìwé tí Waris ti kọ.. | wikipedia | yo |