cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ó bẹ̀rẹ̀ eré orí ìtàgé nínú sinimá àgbéléwò Al Meshakhsaty ní ọdún 2003.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2009,ó kópa gẹ́gẹ́ bi ọmọ ọmọ òṣèré Mohamed SOBhi nínu eré tẹlifíṣọ̀nù Yayamẹ̀yàt Wees We Ahdoh.. | wikipedia | yo |
O se apejuwe ibeere iṣẹ ere rẹ gege bi eyi ti ko ni eto, sugbon ni pa saba bi .el Zhed beere ise re pada gege bi o ni Tiata ninu ere Jimmy's Plan ni odun 2014.. | wikipedia | yo |
Nínú ọdún ná , a fi ṣe ọ̀kan lára àwọn eléré nínú Tamer Hos's TV series Farq TaṢúlèit.. | wikipedia | yo |
In 2015, el Zhed ni ipo ninu ere Alf Leila wa Leila, Mailal el-Ashe, and el BOYOO Asrar.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Karun Ọdún 2017, el Zad fi ara hàn nínu eré tẹlifíṣọ̀nù Fel La La Land, tí a kọ láti ọwọ́ Mustafa Saqr àti olùdarí Ahmed el-Shady.. | wikipedia | yo |
Ètò yí di gbajúgbajà ní ilẹ̀ Egypt's tí a wọ̀ jù lórí ayé lujára .. | wikipedia | yo |
Ni ọdun2018, el Zhed ṣe afihan ninu Sons of Adam.Ni osu keji odun 2019, el Zhed se ere gege bi Gdimila ninu Love Story.. | wikipedia | yo |
Ó fi ara hàn el wá̀ sáyéd el Shahat nínú oṣù karun, pẹ̀lú a fẹ́ lọ́èyàn Ahmed afamy.. | wikipedia | yo |
El Zhed fe Fiwe ni ojo Kọkànlá osu Kesan odun 2019 ayeye ti o tobi, pelu Mohamed HMaki ti o korin .. | wikipedia | yo |
Ni ibi ìjẹfàájì igbéyàwó, á gbé lọsi ilé ìwòsàn nítorí àrù́n inú àgún ní ìgùdà sú́ńn.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2020, el Zad fara hàn nínu eré ìtara The Oríte Machine pẹ̀lú Mahmoud Hemida.. | wikipedia | yo |
Oludari ere na ni Essam Abdel Hamid ti o fara han ni ojo ọla Place .. | wikipedia | yo |
Eré tẹlifíṣọ̀nù òhun gba oríṣiríṣi ọ̀rọ̀ nítorí COVID-19 tòótọ́.. | wikipedia | yo |
Ni Oṣu Keje ọdun 2020, awọn ọkunrin sọrọ o di si ni Ilu Cairo... | wikipedia | yo |
Laura guliamo luyeye Kutika (tí wọ́n bí ní 24 Oṣù Kẹẹ̀jọ, Ọdún 1984) jẹ́ olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Kóngò.Àwọn Ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1984.. | wikipedia | yo |
Becky NGOMA jẹ́ òṣèrébìrin àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Sámbíà.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ olùdarí eré àti agbéréjáde.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn àrùrù ìjád Storytelling and Film with Becky Lévmáa Ara Sámbi Ènìyàn Alààyè AAlààyè | wikipedia | yo |
O ti se opolopo awon ere iriri to fi mo the King's necklace ati le Singe Fou.Àwọn itọkasiàwọn ìtàkùn ìjásóde “Le Collier du má dokòkò in film de Henri Joseph KOKOU BI (Gabon - Fiction)àwọn Ọjọ́ìbí ni 1957àwọn Eniyan Alààyè.. | wikipedia | yo |
Siatta Scott Johnson (tí wọ́n bí ní ọdún 1974) jẹ́ olùdarí àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Làìbéríà.. | wikipedia | yo |
O gbajumọ fun didari ere alaṣeyọri kan ti akọle rẹ jẹ iron Ladies of Liberia.. | wikipedia | yo |
Yàtọ̀ sí ṣíṣe olùdarí eré, ó tún maá n gbé ìròyìn, ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ ọmúah Africa Media.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn ààwọn ládédé New Strategies for Peace Ahead of Elections in Liberia from ‘Big Jues' To 'Ṣíy-y Water,' a Quick Guide To Liberian English Fejal Trains Female Journals to Report on Electoral rẹ̀ 25 Female Journalists Trained in digital security ní 1974 ní àwọn ènìyàn.. | wikipedia | yo |
Marie-Clemence Andriamonta paes (tí wọ́n bí ní ọdún 1959) jẹ́ olùdarí eré, olùgbéréjáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Fránsì àti Madagásíkà.. | wikipedia | yo |
O ti ṣe agbejade ọpọlọpọ awọn ere iriri to fi mọ orilẹgano.. | wikipedia | yo |
, Maella àti l' du bout du monde.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ìtàkùn dlọ́wọ́ Fahavalo, Madagascar 1947àwọn Ọjọ́ìbí ní 1959àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
O gbajumọ julọ fun didari awọn fiimu bii duel a daFá ati fantan Fanga.. | wikipedia | yo |
Yàtọ̀ sí dídarí eré, Diakité tún jẹ́ aṣàpẹẹrẹ aṣọ.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Arlete Guilhermina "Guillermina" Vincente Bombe (tí wọ́n bí ní ọdún 1983) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Mosámbìkì.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn àrù ìjád Arl Guillermina Bombe on IMD ArRIS Bombe On Tathable Arléte Guillermina Bombe on Mubi.. | wikipedia | yo |
KrisÉbẹ́lì Stofẹ́ls jẹ́ olùdarí eré àti agbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàsísí́n.. | wikipedia | yo |
KrisOlùpilẹ̀ ti ṣiṣẹ́ lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù tó fi mọ́ Gẹbọ in die injustice àti Tjiraaa.. | wikipedia | yo |
Orías Mohammed AbdulMajid (Bii ni ojo kẹẹdọgbọn osu keje odun 1995) je osere, modeli ati onisowo lórílẹ̀-ede Uganda.Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹpẹ Aye re won bi manman si ilu Mogadishu ni Somalia.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ jẹ́ AmBasedo Somalia fún orílẹ̀-èdè Saudi Arabia, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ Dókítà.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹrin, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ lórílẹ̀-èdè Egypt.. | wikipedia | yo |
O lo si ile eko giga ti University of Nairobi ni odun 1975 lati kẹkọọ oselu.Iṣẹ o bere ise modeli nigba ti o wa ni ile eko giga.. | wikipedia | yo |
O ti ṣe Rori fun Hahias, Gianni Verlẹ́bú, Calvin Klein, Issey Duke and Donna Gùn.. | wikipedia | yo |
manman bèrè si ni ta jìgì ojú fún àwọn obìnrin ní ọdún 1994.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, ó fi ayaan àti ìkọdy mo fi fi ṣe amko fún ilé iṣẹ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1998, ó kó ipa Marie Btirẹ̀aux nínú eré in the heat of the night.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù kọkànlá ọdún 2010, òun àti Isaac MizRahi Jọ ṣe atọ́kùn fún apá kejì ètò The Fashion show.. | wikipedia | yo |
Lára àwọn eré tí manman ti kópa nínú wọn ni the Human factor, out of Africa, sur]wọ] heart of darkness, no way out, lies of the twins, star trek, the ling incident ati Sígun tó Eden.. | wikipedia | yo |
manman kọ́kọ́ fẹ́ Hassan nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méjìdínlógún.. | wikipedia | yo |
O se igbeyawo pẹlu Sobicer Haywood ni ọdun naa, wọn si bi ọmọbinrin kan ni ọdun 1978.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 1992, o ṣe igbeyawo pẹlu David Dwiwi, wọn si bi ọmọ kan ni ọdun 2000.. | wikipedia | yo |
Bowíé kú ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kìíní ọdún 2016.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
delphe KFouFouani jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Kóngò.. | wikipedia | yo |
Ó maá n ṣiṣẹ́ olùkọ́ni ní ìmọ̀ sinimá ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga University of Saint-Louis, èyí tí ó wà níSẹ̀nẹ̀gàl.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún gbígbé àwọn eré bíi Schmọ́ọ́líe the Deathwatcher, Bridget and Iain àti forgotten BYou jáde.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn àrù ìjáde latest News on Diana Zotítẹ̀lé "Innocent Toke" Preview performanceàwọn Ọjọ́ìbí ní 1977àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
{{Infobox person|name=Juliana Kanyọmọzi|image=|Caption|opóalias|birth:birthdate=nabirth:Place=Uganda|deathdate=date|deathplaceplace=education:Education|Occupation Actress, enter enterf|Nationalityu|u=Credits&Ìdíléàlàfo Tusker Project Fame Kabe-ni}} NETd|title=Laura:Laura káhunde (sister|Ìdílé}} kan}} Kanyọmọ je osere ati olorin ni orile ede Uganda Uganda. | wikipedia | yo |
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ kanyọmọzi jẹ́ mọ̀lẹ́bi pẹ̀lú ọba rukíkì ìiv ti ìlú tòrò.. | wikipedia | yo |
Iṣẹ́ Kanyọmọzi ni obinrin Olórin àkọ́kọ́ tí ó ma gba àmì ẹ̀yẹ ti artist of the year láti ọ̀dọ̀ Pearl of Africa music awards.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 2008 pẹ̀lú eré The Movie’’ èyí tí Henry SSali gbé kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ni osu keta odun 2014, o di ambase fun oriFFF.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2011, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ Pan Africa Artiste láti ọ̀dọ Nigerian Entertainment Awards.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù kejìlá Ọdún 2015, wọ́n fún ní Lifetime Achievement Awards láti ọ̀dọ Diva Awards Africa.. | wikipedia | yo |
O se adajo fun idije orin Tusker Project Fame lati odun 2009 di 2013.igbesi aye re Kanyọmọzi padanu omo re okunrin ti oruko re je Keron Rphael kábùgo ni osu keje odun 2014.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Karun-ún ọdún 2020, ó bí ọmọkùnrin tí ó pè ní Raj.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2013, ìwé ìròyìn ti Big Eye Magazine sọ wí pé Kanyọmọzi ní obìnrin tó rẹwà jùlọ ní gbogbo orílẹ̀ ède Uganda.ami ẹ̀yẹàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Marwa Zein jẹ́ olùdarí eré, ònkọ̀tàn, àti olùgbéréjáde lórílẹ̀-èdè Sudan.. | wikipedia | yo |
Òun ni ó kọ ìwé-ìtàn ti ọdún 2019 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Khartoum Offside.. | wikipedia | yo |
Ó máa ń lọ àwọn iṣẹ́ rẹ̀ láti fi ṣe àgbàwí àti láti fi já fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin.. | wikipedia | yo |
Òun ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ àgbèrè-jáde tí wọ́n pè ní ọ̀rẹ́ production, èyí tí ó wà ní ìlú K.’Sáré.. | wikipedia | yo |
O jẹ okan lara awon meje ti egbe International emerging Film Talent Association (IEFTATA) yan káaayé lati wa nibi ayẹyẹ Cannes Film Festival 2019 gege bi awon alejo pataki.Awon itọkasiàwọn Ìtàkùn ìṣẹ́gun Marwa Zein on on IMD Marwa Zein's Biography on am a film Aawon Eniyan Alààyè.. | wikipedia | yo |
Justine Bitagoye jẹ́ olùdarí eré, ònkọ̀tàn àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Burundi.. | wikipedia | yo |
Ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi agbéròyìn.àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Mounira Mitchala, tí a tún mọ̀ sí Sweet Panther jẹ́ òṣèrébìnrin, akọrin àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Chad.Àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1979.. | wikipedia | yo |
Cleopatra kòHeirwe jẹ́ òṣèré, olórin àti akọ̀wé lórílẹ̀-èdè Uganda.. | wikipedia | yo |
Ó kópa nínu eré The Last King of Scotland gẹ́gẹ́bí Joy ní ọdún 2006.. | wikipedia | yo |
O ko ipa Ebony ninu ere Reflections eyi ti Nana Kagga se adari re.. | wikipedia | yo |
Ó darapọ̀ mọ́ StarTimes Uganda ní oṣù kẹfà ọdún 2019 bí ìkan lára àwọn adarí wọn.Iṣẹ́ ní ọdún 2001, ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ oníjó àti olórin Obsession, ó sì wà níbẹ̀ títí di oṣù kẹta ọdún 2007.. | wikipedia | yo |
Cleopatra bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí agbóhùnsáfẹ́fẹ́ pẹlu 91.3 Capital FM nibi ti o ti ṣe atọ́kùn ètò Drive Time Show.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2013, ó ṣe atọ́kùn ètò fún U-Atil Show pẹ̀lú Radiocity 97FM.. | wikipedia | yo |
Ni Oṣu Kẹsan-an ọdun 2013, oun ati Flavia TuMuṣilir ati Juliana Kanyọmọzi ṣe adajọ fun idije Orin ti Tusker Project Fame ni Kampala.. | wikipedia | yo |
Cleopatra ti kópa nínu oríṣìíríṣìí eré bíi state research Bureau, Se8, changes, be the judge ai yoGera.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2012, reach a hand mu lati soro fun awọn ọdọ ni awọn ile Eko.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, nígbà tí wọ́n fẹ́ gbé eré Changes apá kejì kalẹ̀, òun àti Nick Mutuma, Piverside Makena, nini Waìmúṣẹ àti Patricia Kihoro lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Rob Metẹ́tẹ́ Studios ní Atlanta láti kẹ́kọ̀ọ́ eré ṣisẹ́ daadaa.Ìgbésí ayé rẹ wọ́n bí Cleopatra si idile Jocelyn SewineSan ati Anthony Abam Abawi ni odun 1982.. | wikipedia | yo |
O bi ọmọ binrin ni ojo kejilelogun osu kìíní odun 2014 fun oko rẹ lWanda Jawar.Àṣàyàn eré Reami ẹ̀yẹàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Mosili Makuta jẹ́ òṣèrébìnrin lórílẹ̀-èdè Lèsóth.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Flora Gomes jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Guinea-Bissau.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bi ní ìlú Cadique, orílẹ̀-èdè Guinea-Bissau ní ọjọ́ 31 oṣù kejìlá ọdún 1949.. | wikipedia | yo |
Ó lọ ilé-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Kuba, ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ fíìmù ṣíṣe ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Instituto Cubano del Arte y la Industria Cinematoficos, èyí tí ó wà ní ìlú Havana.eré rẹ̀ kan tí ó ṣe ní ọdún 1988 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Mortu Nega ní àkókò fíìmù àròṣe àti ẹ̀kejì fíìmù gígùn lórílẹ̀-èdè Guinea-Bissau.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà gba àmì-ẹ̀yẹ Oumarou Ganda Prize níbi ayẹyẹ FESPACO ti ọdún1989.Ni ọdún 1992, Gomes darí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Uud Azul di Yonta, èyítí ó jẹ́ wíwò níbi ayẹyẹ Cannes Film Festival ti ọdún 1992.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1949.. | wikipedia | yo |
Yéyamba Wandze Mdrou Ndo? jẹ eré alawada kan ti orilẹ-ede Comoros ti wọn ṣe ni ọdun 2000, eyi ti adari rẹ n ṣe Arsin SoBMy.. | wikipedia | yo |
fíìmù náà ní àkọ́kọ́ fíìmù gígùn ti Comoros.Àwọn olukopa Jacqueline Abdillah Djimba Abrémane DJimby Gùn Hamádì Laher Youssouf Msa Roukia said Arsin SoBM Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Nous Aurons toute la Momo tu Dormir, jẹ́ eré ti ọdún 1977 lórílẹ̀-èdè Mauritania, èyí tí Med Hondo ṣe adarí rẹ̀.Wọ́n bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe fíìmù náà láti 25 Oṣù kejìlá Ọdún 1975 títí di 5 Oṣù kèéta Ọdún 1976.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà dá lóri akitiyan àwọn ẹgbẹ́ Poliist Front láti bọ́ nínú oko-ẹru owó orílẹ̀-ède Spain.. | wikipedia | yo |
Teresa, jẹ́ fíìmù oníṣókí kan ti ọdún 2010 tí wọ́n ṣe ní equatoial Guinea tí olùdarí rẹ̀ n ṣe Thato Rant Migbu, èyí tí Ààjọ ilé-ìkàwé orílẹ̀-èdè Equatorial Guinea ṣe onígbọ̀wọ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Guillermina mekuartu ḿbá ọ̀bọno lẹ́ni tí ó kọ ìtàn eré náà.. | wikipedia | yo |
Àwọn olùkópa rẹ̀ pẹ̀lú Elena Iga, Betty BB, àti Dina Anguesomo.. | wikipedia | yo |
Eré náà jẹ́ àkọ́kọ́ fíìmù Equatorial Guinea tí wọ́n ma ṣe tó sì gùn níbatọ́.Àwọn olùkópa Elena Iga as Teresa Betty K.B. | wikipedia | yo |
Lula Ali Ismail (tí wọ́n bí ní ọdún 1978) jẹ́ olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Djibouti àti Canada.. | wikipedia | yo |
Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti gbé eré jáde lórílẹ̀-èdè Djibouti.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe adarí eré oníṣókí tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Laan ní ọdún 2011.. | wikipedia | yo |
Wọ́n wo fíìmù náà níbi ayẹyẹ Vues d'Afrique Festival tí ó wáyé ní ìlú Montreal ní ọdún 2012, àti ní ọdún 2103 níbi ayẹyẹ FESPACO.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ lórí fíìmù gígùn kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Dhalinyaro, èyí tí òun pẹ̀lú Alexandra Ramniceanu àti Marc Wells dì jọ kọ itan rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Wọ́n kọ́kọ́ gbé eré náà jáde ní oṣù Keèje ọdún 2017.Àṣàyàn àwọn ère rẹ̀ Laan, 2011 Dhalinyaro 2017àwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1978.. | wikipedia | yo |
Umshana ni eré ti ọdún 2015 kan tí wọ́n ṣe lórílẹ̀-èdè Eswatini tí olùdarí rẹ̀ ń ṣe Bi Phathi, èyí tí ilé-iṣẹ́ BI Films ṣètò àgbéjáde rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Awon olukopa ere naa pelu Mbali Dlamini, Delani Dlamini, Lisa Mavuso, Temakrusi Nkambu ati Fineboy Mhlanga.Èyí ni akoko fiimu ti won maa se lede Swati.. | wikipedia | yo |
Gbogbo sise ere naa sii waye ni orile-ede Eswatini.Awon olukopa Mbali Dlamini as Gugu Delani Dlamini as Themba Lisa Mavuso as gugu's friend temakṣì nkam as Precious finẹbọy Mhlanga as uncleàwọn itọkasiàwọn Ìtàkùn ìjásóde Um in YouTube.. | wikipedia | yo |
Vidárúkọ Roumani-Denn (tí wọ́n bí ní ọdún 1950) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Dayán.. | wikipedia | yo |
Fathia Absie jẹ́ òṣèrébìnrin, ònkọ̀tàn, olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Somalia àti Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |