cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
O ni ibatan pẹlu orilẹ-ede Kamẹrúùnù ti o si ti ṣabẹwo sibẹ fun awọn akoko isimi rẹ..
wikipedia
yo
Bresch kó àkọ́kọ́ ipa fíìmù rẹ̀ ní ọdún 2012 nínu Les pápás Du Dimanche.Bresch darapọ̀ mọ́ àwọn olùkópa eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Clem ní ọdún 2015, níbi tí ó ti kópa gẹ́gẹ́ bi Yasmine, ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ Salome..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kẹẹ̀sán Ọdún 2015, Bresch kópa gẹ́gẹ́ bi Therese Marci, ọmọbìnrin kan tí Thomas àti Gabriel gbà toô, nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Plus Belle La Vi..
wikipedia
yo
Tia diagne ni òṣèrébìnrin tí ó kó ipa náà tẹ́lẹ̀ tí ó sì fi sílẹ̀ láti lépa àwọn ànfàní míràn..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017, Bresch kó ipa Charlotte Castillon,nínu eré tẹlifíṣọ̀nù Noir ẹniọ̀mọ̀ùn..
wikipedia
yo
Bresch tún kó ipa Luisa gẹ́gẹ́ bi ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ kan tí ó ní àwọn agbára idán, nínu eré tẹlifíṣọ̀nù ti ọdún 2019 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Mortel..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2020, ó kó ipa Sirley gẹ́gẹ́ bi ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ oníjọ̀gbọ̀n kan nínú eré Mledetta PriVera.yàtọ̀ sí Ede Faranse, Bresch tun maa n sọ èdè Geesi àti èdè Spéì́ì nítététẹ́..
wikipedia
yo
Hortavie Mpondo (tí wọ́n bí ní 27 Oṣù Kẹfà, Ọdún 1992) jẹ́ òṣèrébìnrin, apanilẹ́rìn-ín, àti afẹwàṣiṣẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Kamẹrúùnù.Isẹ̀mí rẹ̀ wọ́n bí Mpondo ní ìlú Lmbe, orílẹ̀-èdè Kamẹrúùnù ní ọdún 1992..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ìwé College Sonara fún ètò ẹ̀kọ́ girama rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010, Mpondo lọ sí ìlú Douala láti kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ biochemistry láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga University of Douala..
wikipedia
yo
Àwọn òbí rẹ̀ wọn kò ba faramọ ààyò iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ pẹ̀lú ìpinnu láti jẹ́ kó di ọ̀mọ̀wé.Mpondo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi afẹwàṣiṣẹ́ tó sì ti ṣe ìpolówó fún ilé-ìtajà BoldMakeUp..
wikipedia
yo
Ó tún tí ṣe ìpolówó fún ilé-iṣẹ́ BGFIBank Group ní Kamẹrúùnù..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017, ó kópa níbi ètò Deïboy Fashion Day, èyí tí ó wáyé ní Alfred Saker College ní agbègbè Deïdo ní ìlú Douala pẹ̀lú àwọn gbajúmọ̀ míràn bíi Tchop Tchop, ẹni tí n ṣe ààrẹ ẹgbẹ́ àwọn atọ́kùn ètò tẹlifíṣọ̀nù ní orílẹ̀-èdè Kamẹrúùnù.Ní ọdún 2017, ó pinnu láti gbájúmọ́ ṣíṣe sinimá àgbéléwò..
wikipedia
yo
Ní ọdún náà, Simeoni kó ipa Amanda nínú ẹrẹ̀ lé Coeur d'ad·za, èyí tí àwọn olùdarí rẹ̀ jẹ́Stéphane Jung àti Sergio Marcello..
wikipedia
yo
Ó kó ipa Samira, ọmọbìnrin àgbà olóyè kan nínu eré oníṣókí ti therry Kamdem kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ elles ní ọdún 2018..
wikipedia
yo
ní ọdún 2019, ó kó ipa Morelia nínu eré oníṣókí kan tí Dante Fox ṣe tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Solo girl..
wikipedia
yo
O sọ di mimo wipe ipa oun ni o pe oun nija julọ..
wikipedia
yo
Kady Traoré (tí wọ́n bí ní 18 Oṣù Kẹẹ̀ta Ọdún 1979) jẹ́ òṣèrébìnrin, olùdarí eré àti agbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Bùrkínà Fasọ̀.Isẹ̀mí rẹ̀ ìlú Bobo-Ulasso ni wọ́n bí Traoré sí ní ọdún 1979..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Isis (Higher Institute of Image and Sound) ní ìlú Ouagadougou.Ó ṣe àkọ́kọ́ ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òṣèré ní ọdún 1998, pẹ̀lú kíkópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù alátìgbà-dègbà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ A nous La Viga, èyí tí Toussaint tiẹ̀ndògoògo darí..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2001, Traoré kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù kan tí Issouf Tapsob ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Les jeunes branchés..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2008, ó kó ipa tímy gẹ́gẹ́ bi ìbátan Ousmane, ẹnití ó n ṣe wọléwọ̀de pẹ̀lú ọlọ́pàá Inspector Marc, nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Super flics.ní ọdún 2014, Traoré ṣe adarí eré táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní a vendredre, èyí tí n ṣe àkọ́kọ́ fíìmù gígùn rẹ̀..
wikipedia
yo
Eré náà sọ ìtàn okùnrin kan tí ó n wá oníbáárà láti ta àwọn àníà rẹ̀ fún títí ó fi pàdé àwọn tọkọtaya kan tí ó sì ló yó ìfẹ́ ìyàwó náà..
wikipedia
yo
Traoré tun dari eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Conflit Conjugal ní ọdún 2017, èyítí ó jẹ́ ọ̀kan nínu fíìmù méjì tí ó..
wikipedia
yo
gba ami-eye ti Suorices Cinema Burkina Faso nibi ayẹyẹ Panafrican Film and Television Festival of Ouagadougou..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2018, Traoré dari ere Prejuge, eyiti o jẹ gbigbe jade latari owo iranlọwọ lati ọdọ Ouaga film Lab..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ agbéréjáde kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Athena Films.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ Traoré ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú akọrin kan tí wọ́n mọ̀ nídi iṣẹ́ rẹ̀ sí Skeykey (tí àbísọ rẹ̀ jẹ́ Serge Martin Bambara) ní 31 Oṣù Kínní ọdún 2008..
wikipedia
yo
Maameyàá Boafo Abiah (tí wọ́n bí ní ọdún 1980) jẹ́ òṣèrébìnrin àti apanilẹ́rìn-ín ọmọ orílẹ̀-èdè Pakí àti Ghana.I rẹ̀ wọ́n bí Boafo ní orílẹ̀-èdè Pasta..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ ṣiṣẹ́ fún United Nations High Commissioner for Refugees..
wikipedia
yo
O lo awọn igba aye rẹ ni awọn orilẹ-ede bii Sudan, Ethiopia, Geneva ati Kenya..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2001, lẹ́hìn tí ó parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀, Boafo lọ sí Amẹ́ríkà láti kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ èdè Faransé àti ìbáraẹnisọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn tí ó gba oyè-ẹ̀kọ́ láti Hood College ní ọdún 2005, ó tún gba owó ìrànlọ́wọ́ ìwé àkò kàn láti kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ eré-ìtàgé ṣíṣe ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Rutgers University..
wikipedia
yo
Boafo tún kẹ́kọ̀ọ́ fún bi Oṣù mẹ́rin ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Marc Bloech University tí ó wà ní ìlú Strasbourg, orílẹ̀-èdè Fránsì.Boafo kó àkọ́kọ́ ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òṣèré nínu eré kan ti ọdún 2012 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Asa, A Beautiful Girl..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, Boafo darapọ̀ mọ́ àwọn olùkópa eré an African City, níbi tí ó ti kó ipa Nana YAA tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ agbéròyìn kan ti yíyálẹgbẹ rẹ̀ ní ìlú Accra nira fún gidigan..
wikipedia
yo
Ipa náà farapẹ́ ti Carrie Braìrẹ̀wẹ̀sì nínu eré Sex and the City..
wikipedia
yo
Ori ẹ̀rọ ayelujara ni wọ́n ti gbe ṣe ayẹwo Boafo fun ipa naa..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, Boafo kópa nínu eré oníṣókí kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Bus Nut..
wikipedia
yo
wọ́n kọ́kọ́ gbé eré náà jáde níbi ayẹyẹ San Francisco Film Festival.Ní ọdún 2015, Boafo kó ipa kékeré kan nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Family Fang..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, ó kópa nínu àwọn eré oníṣókí kan tí àkọ́lé wọn jẹ́ New York, I Love You àti Olive..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2017 sí 2018, ó kó ipa bi Paulina nínu eré School Girls, èyítí wọ́n ṣe láti farapẹ́ eré míràn tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ mean Girls..
wikipedia
yo
Fun iṣẹ takuntakun rẹ̀, wọn yan Boafo fún àmì-ẹ̀yẹ Lucille Lortell Award àti Los Angeles Drama Circle Award fún òṣèré tí ó dára jùlọ, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ ti Drama Desk Award..
wikipedia
yo
O ko ipa abẹ́nà Kami gege bi alárùn HIV kan ninu ere Chicago Med..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, ó kópa gẹ́gẹ́ bi olùṣèwádìí kan nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Bluff City Law..
wikipedia
yo
Boafo tún kó ipa Zainab nínu eré tẹlifíṣọ̀nù ti ọdún 2020 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Ramy.Boafo ti ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Jeremiah Abiah, ó sì n gbé ní ìlú New York..
wikipedia
yo
Leila Hadioui (tí wọ́n bí ní 16 Oṣù Kínní, Ọdún 1985) jẹ́ òṣèrébìnrin, afẹwàṣiṣẹ́ àti atọ́kùn ọmọ orílẹ̀-èdè Mòrókò.Itọ̀ rẹ̀ wọ́n bí Hadioui ní ìlú Casablanca ní ọdún 1985..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ tí ń ṣe Noureddine Hadioui ni ó máa ń pe ìwa fún mọ́ṣiṣinù Hassan II tí ó wà ní ìlú Casablanca..
wikipedia
yo
Ó fẹ́ràn Oge ṣíṣe láti ìgbà kékeré rẹ̀, tó sì máa wo àwọn ètò tẹlifíṣọ̀nù tí ó dá lórí Oge ṣíṣe..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún, ó ṣe àkọ́kọ́ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi afẹwàṣiṣẹ́..
wikipedia
yo
Hadioui fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ aṣàpẹẹrẹ fún ti ètò ìfihàn CAFtan 2007..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007, ó dá ilé-ìtajà aṣọ àwọn obìnrin sílẹ̀.ní ọdún 2010, Hadioui kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Les Enat Terribles de Casablanca, èyítí AbdelKarim derkaoui darí..
wikipedia
yo
ó ti ṣe atọ́kùn ti ètò oge kan tí wọ́n pè ní Saba’(te..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ó kópa nínu sinimá tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Sara, èyítí Said NAciri darí..
wikipedia
yo
Ó ti hàn nínu àwọn sinimá àgbéléwò, eré alátìgbà-dègbà àti àwọn ètò ìfihàn lórí tẹlifíṣọ̀nù..
wikipedia
yo
Chantal Youdum jẹ́ olùdarí eré àti agbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè KaKamẹrúùnù rẹ̀ ní ọdún 2011, Youdum ṣẹ̀dá eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Au Coeur de l'amour, èyítí wọ́n gbé sáfẹ́fẹ́ lóri ìkànnì TV5 àti Canal 2..
wikipedia
yo
Eré náà dá lóri ọ̀dọ́mọbìnrin kan tí kò mọ́ bàbá rẹ̀, ó sì ṣàfihàn àwọn òṣèré bíi Valérie Duval, ẹnití ó rọ́pò òṣèrébìnrin Rouegú..
wikipedia
yo
Youdum darí fíìmù ti ọdún 2014 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Sweet Dance, èyí tí n ṣàfihàn Pelagie Nguiateu àti Alain Bọmọ Bomo.Ní ọdún 2016, wọ́n yan Youdum gẹ́gẹ́bí ọ̀kan nínu àwọn obìnrin méje tí wọ́n mú ìdàgbà bá ìwé-ìtàn kíkọ ní ilẹ̀ Áfríkà..
wikipedia
yo
O sise gege oluṣakoso ipele fun ti ere Aisa ni ọdun 2017, eyiti Jean ròkè patoudem dari..
wikipedia
yo
Eré náà dá lóri ìtàn ọ̀dọ́mọbìnrin kan tí ó ní láti lọ gbé pẹ̀lú bàbá rẹ̀ ní abúlé míràn..
wikipedia
yo
Wọ́n kọ́kọ́ gbé eré Assa jáde níbi ayẹyẹ Panafrican Film and Television Festival of Ouagadougou àti Vues d'Afrique Festival..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017 yìí bákan náà, Youdum darí eré Reveve Corrompù..
wikipedia
yo
Èrè náà dá lórí ọdọmọkunrin kan tí ó fi abúlé rẹ̀ sílẹ̀ láti lọ gbé ní ààrin ìlú nírètí láti ṣoríire níbẹ̀..
wikipedia
yo
Eré náà gba àmì-ẹ̀yẹ níbi ayẹyẹ Érans Noirs Festival ti ọdún 2018.Ní ọdún 2018, Youdum lọ́wọ́sí ṣiṣẹda eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Mimi La Bonne, pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Francis tene..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe ìfihàn eré náà níbi ayẹyẹ Festival International de Films de femmes ní ìlú Yaoundé.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Tânia Cefira Gomes Burity (tí wọ́n bí ní 28 Oṣù Kẹẹ̀sán, Ọdún 1978) jẹ́ òṣèrébìnrin, olùgbéròyìn, atọ́kùn, àti afẹwàṣiṣẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Àngólà.I rẹ̀ wọ́n bí Burity ní ìlú Luanda, orílẹ̀-èdè Àngólà..
wikipedia
yo
Ó gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ Ìgbéròyìn láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Instituto Medio de Seindala de Luanda (IML) kí ó tó tún kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Instituto Superior PrivAdó de Angola..
wikipedia
yo
Burity ti ṣe iṣẹ́ olùgbéròyìn bẹ́ẹ̀ lọ sí ti ṣiṣẹ́ rí ní ilé-ìtajà ṣáájú kí ó tó bọ́ sídi iṣẹ́ òṣèré.Láti ọdún 2001 sí 2004, òun ni atọ́kùn ètò tẹlifíṣọ̀nù kan tí wọ́n pè ní Angola dá Sorte..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2001, Burity kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Vidal Ocultas..
wikipedia
yo
Ní ọdún tí ó tẹ̀le, ó kó ipa ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ kan tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ Djamila nínu eré Reviravolta..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2005, Burity kó ipa Cláudia nínu eré Sede de Viver..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2005 sí ọdún 2006, ó kó ipa EUe nínu eré tẹlifíṣọ̀nù oníṣókí kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ 113..
wikipedia
yo
Òun ni olùkéde àti olóòtú ìròyìn fún ètò rédíò kan tí wọ́n pè ní àáá nó Angola láti ọdún 2005 sí ọdún 2006..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007, òṣèrékùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ n ṣe Fredy Costa sí ọwọ́ rẹ̀ lé Burity lóri, èyí tí ó mú láti má Lee ṣiṣẹ́ fún Oṣù méjì tí wọ́n sì dá ẹ̀wọ̀n Oṣù mẹ́fà fún Costa náà.Ní ọdún 2009, Burity kó ipa Camila gẹ́gẹ́ bi olùṣòwò nínu eré Minha Terra, Minha Mae..
wikipedia
yo
Laarin odun 2010 si 2012, oun ni Olùkede ati oludari eto redio kan ti o wa fun awon omode ti won pe ni Karibrin na Radio..
wikipedia
yo
Burity tún ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi afẹwàṣiṣẹ́, ó sì ti ṣe atọ́kùn níbi ìdíje ẹwà Miss Luanda ti ọdún 2011..
wikipedia
yo
Ó kó ipa gẹ́gẹ́ bí agbani-nímọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ oge nínú eré kan ti ọdún 2012 tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Windeck..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ó tún ṣe atọ́kùn níbi ètò ìfihàn Big Brother Angola..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, Burity ṣe alága ìgbìmọ̀-onígbẹ̀ẹ́jọ́ fún ètò Casting JC Models àti Casting para Actores Agência Útima. rẹ̀ ní Dicla Burity, ẹni tí òun náà ń ṣiṣẹ́ atọ́kùn ètò tẹlifíṣọ̀nù..
wikipedia
yo
Ìlú Lisbon ni Tânia Burity fi ṣe ibùgbé, ó sì ti ní àwọn ọmọbìnrin méjì.àṣàyàn àwọn eré àko Ìtọ́kasíàwọn ànilè ìjáde já Tânia Burity at the Internet Movie Database.Àwọn ènìyàn Alààyè Ọjọ́ìbí ní 1978..
wikipedia
yo
Albertine N'Guessan Zjẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ Lou (Ó di olóògbé ní 22 Oṣù Kẹẹ̀rin, Ọdún 2016) tí jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Côte d'Ivoire.Isẹ̀mí rẹ̀ N'Guessan kẹ́kọ̀ọ́ ní National Institute of Arts (ina) ní ìlú Abidjan..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1972, ó kópa pẹ̀lú Bitty Moro, Aboufani Cyprien Toure àti Noel guie nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Les Gens des Marais, èyítí ònkọ̀tàn eré náà n ṣe Wole Soyinka tí olùdarí rẹ̀ síì jẹ́ Jean Faòkùnkùnl..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1977, N'Guessan kópa nínu eré The Tragedy of King Christophe, èyí tí Aimé Césaire kọ, tí olùdarí rẹ̀ síì jẹ́ bitty Moro..
wikipedia
yo
Laarin ọdún1986 sí 1987, ó kópa nínu eré Une meme a ẹgbẹ̀rin, eré tí kò Kojọ Éts ṣe àgbéjáde rẹ̀ tí François Campeaux síì jẹ́ ònkọ̀tàn eré náà.Ní ọdún 1984, N'Guessan kópa nínu eré Abani, èyí tí Maa Ecare darí..
wikipedia
yo
Ní ọdún tí ó tẹ̀le, ó kópa nínu eré Vges de femmes láti ọwọ́ olùdarí kan náà.Ní ọdún 2000, N'Guessan kópa gẹ́gẹ́ bi ìyá sí Osessei nínu eré àdánmanman, èyí tí Roger gan Mbala ṣe adarí rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Sah Sandra ní ọdún 2009, gẹ́gẹ́ bi ìyáàgbà sí Sassi..
wikipedia
yo
N'Guessan ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi olùkọ́ni ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga National Institute of Arts and Cultural Action tí ó wà ní ìlú Abidjan ṣaájú kí ó tó pinnu láti fẹ̀yìntì..
wikipedia
yo
Wọ́n kàá kún ọ̀kan lára àwọn òṣèrébìnrin ìṣaájú ní orílẹ̀-èdè Côte d'Ivoire..
wikipedia
yo
Noufissa Benchehida (tí wọ́n bí ní 23 Oṣù Kẹẹ̀wá Ọdún 1975) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Mòrókò.Isẹ̀mí rẹ̀ Wọ́n bí Benchehida ní Mòrókò ní ọdún 1975..
wikipedia
yo
O kẹkọọ ni ile-iwe Cours agbon ti o wa ni ilu Paris..
wikipedia
yo
Benchehida gba oye-ẹkọ ninu imọ ere-itage lati ile-ẹkọ giga Conservatory of Casablanca, bẹẹ lo si tun lọ si Ile-ẹkọ École supérieure d'hhhrierie et de tourisme a Montpellier.Benchehida kó àkọ́kọ́ ipa fíìmù rẹ̀ ní ọdún 2004 nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ SyRiana tí olùdarí rẹ̀ síì n ṣe Stéphane Cagan..
wikipedia
yo
Ó di gbajúmọ̀ lẹ́hìn tí ó kó ipa Zineb Hejinu gẹ́gẹ́ bi ọlọ́pàá nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ El Kdia ní ọdún 2006..
wikipedia
yo
Ó sọ di mímọ̀ wípé òun gbádùn kíkọ ipá náà ṣùgbọ́n òun kò fẹ́ láti máa ṣe irúfẹ́ ipa bẹ́ẹ̀ ní gbogbo ìgbà, àti pé òun fẹ́ láti kópa nínú àwọn eré oníjà..
wikipedia
yo
Níkan náà ní ọdún 2006, ó kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Moulouk Attawaif..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2011, Benchehida kó ipa olú-ẹ̀dá-ìtàn nínu eré Agadir Bombay, gẹ́gẹ́ bi obìnrin kan tí ó n ṣe àgbàwí fún àwọn obìnrin ẹgbẹ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, ó kópa nínu fíìmù Aida.Ní ọdún 2016, Benchehida kópa nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ A La Recherche du Pouvoir perdu ("sise àwárí agbára tí ó sọnù"), èyí tí Mohammed Ambad Bensouda darí..
wikipedia
yo
Iṣe takuntakun rẹ̀ ninu eré naa lo fun ni ami-ẹyẹ ti Golden Sotigui nibi ayẹyẹ Sotigui Awards ti ọdún 2017..
wikipedia
yo
Sheila Munyiva (tí wọ́n bí ní 27 Oṣù Kẹẹ̀ta Ọdún 1993) jẹ́ òṣèrébìnrin àti olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Kẹ́nyài rẹ̀ wọ́n bí Munyiva ní ọdún 1993 ní ìlú Nairobi..
wikipedia
yo
O maa n wo ere Hannah Montana lọpọlọpọ nigba ti o wa lọmọ..
wikipedia
yo
O maa n se abẹwo si Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan loorekoore nitori wipe nibẹ ni iya rẹ n gbe..
wikipedia
yo
Munyiva kọ́ ẹ̀kọ́ láti jẹ́ òṣìṣẹ́ ìròyìn ní ìbẹ̀rẹ̀ ṣaájú kí ó tó fún sí ṣíṣe fíìmù..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn ìparí ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó tún bẹ̀rẹ̀ sí ní lọ sí àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kan láti lẹ̀ túnòwúrọ̀ dára sí gẹ́gẹ́ bi ònkọ̀tàn.Ní ọdún 2018, Munyiva kó ipa Ziki nínu eré Rafiki..
wikipedia
yo
Eré náà dá lóri ìwé-ìtàn kan tí Monica Arac de Nyeko kọ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Jambula Tree, tó síì n ṣàlàyé ìfẹ́ tí ó n bẹ láàrin àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin méjì kan ní ìlú tí ìbálòpọ̀ ẹlẹ́yà kan náà ti jẹ́ èèwọ̀..
wikipedia
yo