cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ó kópa gẹ́gẹ́ bi ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga kan tí ó yọ́ ìfẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ẹgbẹ́ rẹ̀ ṣùgbọ́n ti eré ìfẹ́ àwọn méjèèjì padà já sí ìkorò nígbẹ̀yìn..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn ipa rẹ̀ nínu fíìmù náà, Estifanos pinnu láti dáwọ ẹ̀kọ́ rẹ̀ dúró náà láti lè gbájúmọ́ iṣẹ́ òṣèré, bótilẹ̀jẹ́pé ó ṣe ìpinnu láti padà sí ìdí ẹ̀kọ́ rẹ̀ bí kò bá rí kíọdún nídi iṣẹ́ òṣèré náà.Estifanos ló fún ìdánilẹ́kọ̀ọ́ nípa eré ṣíṣe fún Oṣù mẹ́ta ní ilé-ẹ̀kọ́ Department of Cultural Affairs..
wikipedia
yo
Estifanos kó ipa ti Hunaz nínu eré tẹlifíṣọ̀nù alátìgbà-dègbà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ hareg gẹ́gẹ́ bi ọmọbìnrin kan tó ní àwọn olólùfẹ́ méjì..
wikipedia
yo
Madouline Idrissi (tí wọ́n bí ní 10 Oṣù Kẹẹ̀ta, Ọdún 1977) jẹ́ òṣèrébìnrin àti apanilẹ́ẹ̀rín ọmọ orílẹ̀-èdè Mòrókò.Itọ̀ rẹ̀ wọ́n bí Idrissi ní ìlú Rabat ní ọdún 1977..
wikipedia
yo
Idrissi fẹ́ràn láti máa jíjó ballet, èyí tí ó mú kí ó forúkọsílẹ̀ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa ijó ballet náà ní àkókò ìgbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rin..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó pé ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún, ó lọ sí ìlú Montreal láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣàkóso òwò..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ìfẹ́ sí ṣíṣe eré sinimá lẹ́hìn tí ó tẹ̀lé ọ̀rẹ́ rẹ̀ kan lọ sí ibi ìdíje eré ìtàgé kan..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2003, ó kó àkọ́kọ́ ipa fíìmù rẹ̀ nínu eré El Bandia..
wikipedia
yo
Ó kópa gẹ́gẹ́ bi Habiba nínu fíìmù ti ọdún 2006 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ La Symphonie marocaine tí olùdarí eré náà síì jẹ́ Kamal Kamal..
wikipedia
yo
Idrissi kó ipa Jamila nínu fíìmù ti ọdún 2009 kan tí Souad Lodou ṣe tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Camille and Jamila..
wikipedia
yo
O ko ipa Rihanna, gege bi ọmọbinrin alaisan kan ninu ere Chgase ni odun 2010, eyiti o sokun fa gbigba akoko ami-eye rẹ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, Idrissi tún kó ipa Myriam, nínu eré Divinï, eré tí Hohou benyamina darí..
wikipedia
yo
Eré náà gba àmì-ẹ̀yẹ ti Caméra d'Or níbi ayẹyẹ Cannes Cannes Film Festival..
wikipedia
yo
Ní Oṣù kọkànlá, Ọdún 2019, Idrissi ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú òṣèrékùnrin Aziz Hattab ..
wikipedia
yo
Sonna Seck (tí àbísọ rẹ̀ jẹ́ Maimouna Seck tí wọ́n bí ní ọdún 1985) jẹ́ òṣèrébìnrin, akọrin àti apanilẹ́rìn-ín ọmọ orílẹ̀-èdè Guinea.Itọ̀ rẹ̀ wọ́n bí Seck ní ìlú Mamou ní ọdún 1985..
wikipedia
yo
Láti ìgbà kékeré rẹ̀ ni ó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ àwọn orin àṣà níbi àwọn ayẹyẹ ìgbéyàwó àti ìrìbọmi..
wikipedia
yo
Seck lọ sí ilé-ìwé Lycée Ymba fún ètò-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007, ó lọ́wọ́sí dídásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèré kan tí wọ́n pè ní Djouri Djaama Acting Trourou, ó síì kó àkọ́kọ́ ipa fíìmù rẹ̀ nínu fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Yo-Allah Feounou In..
wikipedia
yo
Seck kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù nípasẹ̀ ẹgbẹ́ Djouri Djaama..
wikipedia
yo
Lára wọn ni Guigol Nretii Dkiki, Mouyide Allah, àti Ahh WaJàmáíkà ..
wikipedia
yo
Àṣeyege àwọn fíìmù wọ̀nyí fún ẹgbẹ́ náà ní ànfàní láti ṣe àwọn iṣẹ́ míràn káàkiri orílẹ̀-èdèọ.Ó kópa gẹ́gẹ́ bi akọrin nínu eré rẹ̀ kan tí ó ṣe tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Endan-PAàkúnya..
wikipedia
yo
Níbẹ̀ ló ti kọ orin kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ṣaya.Seck tún ti kọ àwọn orin bíi Bounguai, Sodanelan, àti Inmedjìn..
wikipedia
yo
Ó ṣe àgbéjáde orin rẹ̀ tí ó gbajúmọ̀ jùlọ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Tourou Tourou ní ọdún 2015, tí orin náà síì tàn káàkiri orílẹ̀-èdè Guinea àti àwọn agbègbè rẹ̀..
wikipedia
yo
Ààrẹ orílẹ̀-èdè náà, Alpha Conjáde, mẹ́nuba orin náà nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìyẹ́sí àwọn obìnrin ti ọdún 2018..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2020, Seck bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ àdáṣe rẹ̀ lábẹ ilé-iṣẹ́ orin Soudou dáàrdja prod ..
wikipedia
yo
Àkọ́kọ́ orin àdákọ rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ ń ṣe Midho Yidhouma jẹ́ orin ìfẹ́ tí ó kọ fún ọkọ rẹ̀ tí n gbé ní Amẹ́ríkà.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn ààwọn ìjáde YouTube Channe Channeláwọn ènìyàn ìkò Ọjọ́ìbí ní 1985..
wikipedia
yo
Milka Irene soObya jẹ́ òṣèré àti òṣèlú ní orílẹ̀ èdè Uganda tí ó gbajúmọ̀ fún ipa Monica tí ó kó nínú eré Dáveption àti ipa fífi aripa nínú eré Power of legacy..
wikipedia
yo
Ó díje fún ipò ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ aṣojú fún àwọn obìnrin fún ìlú Jinja.Iṣẹ́ eré àkọ́kọ́ ti Solaobya ma ṣe ní eré Makuder Junction..
wikipedia
yo
O di gbajumọ gẹgẹ bi elere nigba ti o ṣe Monica ninu ere Leeption ti o se lati inu ọdun 2013 titi di 2016..
wikipedia
yo
O ti kopa ninu awon ere bii The Rungu Girls, HoneyMOON is kóattedted, Christmas in Kampala and Taxi 24 eyi ti Akpor Onira se adari fun..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, ó kópa nínu eré Power of Legacy gẹ́gẹ́ bi fífi Aripa..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2020, ó díje fún ipò Aṣojú àwọn obìnrin amòfin ní ìlú Jinja.àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣeÌGBÉSÍ ayé rẹ̀ wọ́n bí Solaso sí ìlú Jinja..
wikipedia
yo
O lo si ile eko mbodo High School ati Mariam High School ki o to te siwaju si ile eko giga ti Kabego University nibi ti o ti gboye ninu imo procurement and Rábàstics Management.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Eleanor Vaal Nanṣíbọ́ Nabwi jẹ́ òṣèré àti adarí eré lórílẹ̀-èdè Uganda..
wikipedia
yo
O gbajumọ fun ipa ti o ko ninu ere The Hotel, Rain, Beneath the lies- the series ati bed of thorns gege bi oludari awon ere naa..
wikipedia
yo
Ó dá ilé iṣẹ́ tó ma ń gbé eré jáde kalẹ̀ pẹ̀lú oko rẹ̀, ó sì pèé ní Nabwi films.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹpẹ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọn bí Nabwí sí ilé ìwòsàn ti sir Albert cook Meolong Hospital..
wikipedia
yo
Kẹfà Sempangi, Orúkọ Ìyá Rẹ̀ sì jẹ́ Jane Frances Nkamya..
wikipedia
yo
Òun ni ọmọ kẹta nínú àwọn ọmọ márùn-ún ti àwọn òbí rẹ̀ bí..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ ni olùdásílẹ̀ ilé ìjọsìn ti Presbyterian Church ní orílẹ̀ èdè Uganda..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé èko ṣgéV Girls' Primary School àti seeta High School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti sik Manipal University níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ Science.iṣẹ́ Nabwi bẹ̀rẹ̀ eré ṣiṣẹ́ nígbà tí ó sì wà ní ọmọdé.. *
wikipedia
yo
Ó kópa nínu eré K-Files nígbà tí ó sì wà ní ilé ìwé..
wikipedia
yo
Ó kópa nínú eré The Hostel èyí tí ó sọ̀rọ̀ nípa ìgbésí ayé àwọn ọmọ ilé ìwé Yunifásítì..
wikipedia
yo
Ó kópa nínu eré Kobasíwála ti Emmanuel IkuBéṣe ṣe adarí rẹ̀..
wikipedia
yo
Lára àwọn ère tí ó ti ṣe ní reach a hand, #Family, beneath the lies, watch over me ati bed of thorns..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, ó gba àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bi òṣèré tó dára jù lọ níbi ayẹyẹ Uganda Film Festival Awards..
wikipedia
yo
Wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ Best Ure Award láti ọ̀dọ London Aright Film Festival Award àti Africa Focus Award fún ipa tí ó kó nínú eré Araking of D.igbesi ayé rẹ̀ ó jẹ́ ìyàwó fún Matthew Nabwiso tí ó jẹ́ òṣèré àti olórin, wọ́n sì ti bí ọmọ mẹ́rin.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Leila Naukábì (bíi ní ọdún 1993) jẹ́ òṣèré àti ajìjàgbara fún àwọn obìnrin ní orílẹ̀ èdè Uganda..
wikipedia
yo
Ní ọdún náà, wọ́n tún yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tó dára jù lọ láti Zulu Africa Film Academy Award fún ipa tí ó kó nínú The Forbidden..
wikipedia
yo
O gba ami eye osere binrin to dara ju lo lati odo Udada Women's Film Award ni ojo ogun, osu Kẹwàá odun 2018.Ni odun 2019, won yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré binrin tó dára jù lọ láti ọ̀dọ The African Film Festival (Taff) Awards àti Lake International Film Festival (Lipff).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Stella NantuMB jẹ oṣere ati omidan Uganda ni ọdun 2013..
wikipedia
yo
Oun ni aṣoju Uganda ni Big Brother Africa ni ọdun 2014.ibẹrẹ pẹpẹ aye ati ẹkọ rẹ wọn bi Stella si idile Angela yíjúYonga ati Rogers nserékàn ni ọdun 1991 ni orile ede Uganda..
wikipedia
yo
òun ni àbíkẹ́yìn nínú àwọn ọmọ méjìlá tí àwọn òbí rẹ̀ bí..
wikipedia
yo
O lo si ile eko buGanda Road Primary School ati kábọ̀Já International Secondary School ki o to te siwaju si ile eko giga ti University of Greenwich nibi ti o ti gboye ninu imo Business Comdting ni odun 2012.Iṣẹ ni ọdun 2013, nigba ti o wa ni ọmọ ọdun mejilelogun, o lo fun idije Omidan Uganda, o si gbe igba orókè ninu idije naa..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 2014, ó gboyè omidan tó gbajúmọ̀ jù lórílẹ̀-èdè Uganda..
wikipedia
yo
Ni oṣu Kẹsan-an, ọdun 2013, o ṣe aṣoju fun Uganda nibi ìdíje Omidan agbaye..
wikipedia
yo
O kopa nibi idije Big Brother Africa ni ọdun 2014 gẹgẹ bi aṣoju fun Uganda..
wikipedia
yo
ellah ti kópa nínú eré fiimu, ó sì ti ṣe atọ́kùn ètò lórí Oriapá..
wikipedia
yo
Ó kó ipa Isabella Arroyo nínú eré el Cuer del dẹ́ṣẹ̀o ní ọdún 2016..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, ó ṣe atọ́kùn ètò Scoop on Scoop lóri Urban TV..
wikipedia
yo
O jẹ ikan lara awon adajo fun idije Omidan Uganda ni ọdun 2018..
wikipedia
yo
Òun ní ìgbà kejì Ààrẹ fún Africa Music Industry Awards.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Wale Adebayo jẹ́ òṣèrékurìn, adarí eré àti olùgbéré-jáde tí wọ́n bí ní ìlú Abẹ́òkúta ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, amo àwọn òbí rẹ̀ qaq láti Ìpínlẹ̀ Òndó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ẹ̀-ẹ̀kọ́ rẹ̀wale lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ilé-ẹ̀kọ́ girama ti “Satellite Town” ní Ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó dàgbà sí..
wikipedia
yo
Ó lọ kọ́ ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ .Iṣẹ́ rẹ̀wale di ìlú-mọ̀ọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré Ṣàngó gẹ́gẹ́ bí olú ẹ̀dá-ìtàn..
wikipedia
yo
Ó ti gbé àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọ̀kan eré bíi Makabba àti double game, the legendary African King àti Wàyíring ..
wikipedia
yo
Ó sì tún ti darí eré onípele àtiní-dègbà bí Binta and Friends àti pápá Ajasco and company lábẹ́ ilé-iṣẹ́ Wale Aedy.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Sarah Sayonto kísàwuzi je osere ni orile ede Uganda ti o gbajumọ fun ipa ti o ko ninu ere Leeption gege bi nalweyiyi.ise kísàwuzi di gbajumọ fun ipa nalwe ti o ko ninu ere Noògiri lati odun 2013 di 2016.. 2016..
wikipedia
yo
O gba ami eye oṣere binrin to dara jù lọ fun ipa ti o ko ninu ere naa lati ọdọ Uganda Entertainment Awards ni ọdun 2015..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, ó kó ipa Mama Stella nínu eré Araking of thorns àti ipa Barbara Baltte nínú eré Power of Legacy.àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣeàmì ẹ̀yẹàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mariam ńdágire (bíi ní Ọjó kẹrìndíndínlógún Oṣù karùn-ún ọdún 1971) jẹ́ olórin, òṣèré àti olùdarí eré lórílẹ̀-èdè Uganda.ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Mariam sí ìlú Kampala ní orílẹ̀ èdè Uganda sí ìdílé Sarah Nabbutto àti Prince Kèitoito Sobawen
wikipedia
yo
O lo si ile eko buGanda Road Primary School àti Kampala High School ki o to te siwaju si ile eko giga ti makere University.Iṣẹ ndagirẹ̀ bẹrẹ ere ori itage nigba ti o wa ni omo odun meedogun..
wikipedia
yo
Ó darapọ̀ mọ́ Black Pearls ní ọdún 1987, ibẹ̀ sì ni ó ti kó eré àkọ́kọ́ rẹ̀ tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Yenebo Y'ad..
wikipedia
yo
Òun àti Kato Luwamá àti AhRAF Simwogẹ́rere jọ dá ẹgbẹ́ diamonds' Edúrúmble kalẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, ó jẹ́ ìkan lára àwọn tí ó ṣe adájọ́ fún ètò àmì ẹ̀yẹ ti Africa Magic Viewers' Choice Awards AMVCA gbé kalẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, ó jẹ́ ìkan lára àwọn tí ó ṣe adájọ́ fún Golden Movie Awards Africa.Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣe muloNGO WWA (1997) bámú—G (1998) Onkye (2000) Kailasúnmọ́Sọ́ọ̀lù (2001) Kodeaneane (2002) Abakazi Uwibá (2003) Akuji (2004) Aoriláboko (2007) Maama (2007) Byonna TV (2009) Majanwa (2009) Oly' Oly (2012) KíKìkì onVuma (2014) Ki'ọmú (2016) Eye Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Bettinah Tiana (bíi ní Ọjọ́ Kẹwàá Oṣù kọkànlá Ọdún 1993) jẹ́ òṣèré, Rorich àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórílẹ̀ èdè Uganda..
wikipedia
yo
O gbajumọ gege bi atọkun fun eto Youth Voice, Be my date ati the style project..
wikipedia
yo
Ó kó ipa Rhona nínu eré The Hostel.Iṣẹ́ timeric bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe atọ́kùn fún ètò Youth Voice láti ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún..
wikipedia
yo
Tijúbà bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe gẹ́gẹ́ bi Rhona ní eré The Hostel..
wikipedia
yo
Òun ni ó ṣe atọ́kùn fún ayẹyẹ Unaa Convention ní ìlú Washington D.C..
wikipedia
yo
O darapọ mọ Creative Industri Group ni ọdun 2017, gege bi Rori fun wọn.Eko timeric gboye ninu imo iroyin lati Ile Eko giga ti Cavendish University.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Aisha KWashangi tí orúkọ ìnagi rẹ̀ jẹ́ Lady Aisha jẹ́ òṣèré, olórin àti gbígbé jáde eré lórílẹ̀-èdè Uganda Uganda..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ ẹgbẹ Bakayimbira Drama tors.iṣẹ Aisha ti ṣe ere fun ọdun to le ni ogun..
wikipedia
yo
Ó kópa nínu àwọn eré bíi The Last King of Scotland, Byansi ,the Pebles àti mistakes Galz Do..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, ó gbé eré Kemi jáde, èyí sì ni eré tí ó ma kọ́kọ́ gbé jáde..
wikipedia
yo
Wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré tó dára jù lọ fún ipa tí ó kó nínú eré Honhonoble ní ọdún 2002, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tuntun tó dára jù lọ láti ọ̀dọ Pearl of Africa Music Music.Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣe ṣe EAbẹ́jábẹ̀rẹ̀ yá Kony Kinvmanmányi (The MoMoito) enyana ekùtù Nwuwú The Hondura sí ayé rẹ̀ Aisha jẹ́ ìyàwó fún Charles Ṣgbẹ̀gbẹ̀, ó sì ti bí ọmọ kan.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Nisha kalema (Bii ni odun 1993) je osere, Akowe ati Olugbe jade ere lórílẹ̀-ede Uganda..
wikipedia
yo
O gba ami eye gege bi osere binrin to dara ju lo lati odo Uganda Film Festival Award ni odun 2015, 2016 ati 2018 fun ipa ti o ko ninu ere The Tailor, Freedom ati Verónica's wish.ise kalema di gbajumo osere nipa ere Galz about town..
wikipedia
yo
O ko ipa olori awon aṣẹ́wó ti oruko re je Clara ninu ere naa..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, Hassan Mageye fi kalẹ̀ma ṣe Grace nínú eré The Grace..
wikipedia
yo
Eré náà sì lọ jẹ́ kí ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tó dára jù lọ tí ó kọ́kọ́ gbà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, ó gba àmì ẹ̀yẹ kejì gẹ́gẹ́ bi òṣèré bìnrin tó dára jù lọ fún ipa Amelia tí ó kó nínu eré Freedom..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, ó kó ipa Verónica nínu eré Verónica's wish..
wikipedia
yo
Eré náà sì lọ jẹ́ kí ó gba àmì ẹ̀yẹ kẹta gẹ́gẹ́ bi òṣèré bìnrin tó dára jù lọ..
wikipedia
yo
Eré náà sì ti gba àmì ẹ̀yẹ mẹ́ẹ̀sán.Èkó kalẹ̀ lọ sí ilé ẹ̀kọ́ St Charles Lwanga Primary School àti Kainabiribiri Secondary..
wikipedia
yo
Ó gboyè nínú ìmọ̀ ìròyìn láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Buganda Royal Institute of Business and Technical Education ní ọdún 2013.àṣàyàn àwọn eré rẹ̀nínu Ori Oriweeré Ori ìtàgé ẹ̀yẹ Ìtọ́kasíàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Monica Jacobs Birwinyo (bíi ni ọjọ́ kẹrin osù kẹfà ọdún 1990) jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórílẹ̀ èdè Uganda..
wikipedia
yo
Ó ti kópa nínu àwọn eré bíi Imbabazi, The Pardon, Beauty to Ashes , Because of U, 5@home, Honoraz àti Mela and Zansanze
wikipedia
yo
ní ọdún 2012, òun àti Monica Birwinyo, Irene Aumpta àti Jacob NSaarun ṣe atọ́kùn fún ètò Movie Digest Show..
wikipedia
yo
Ó kópa nínu eré The Pardon gẹ́gẹ́ bi Muhoza.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Manon Bresch (tí wọ́n bí ní 4 Oṣù Kínní, Ọdún 1994) jẹ́ òsèrésurun ọmọ orílẹ̀-èdè Fránsì àti Kamẹrúùnù.Isẹ̀mí rẹ̀ Bresch kọ́ ẹ̀kọ́ eré-ìtàgé ní ilé-ìwé Cours ṣon, tí ó wà ní ìlú Paris fún ọdún méjì gbá́n..
wikipedia
yo