cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Abojijì ọmọtayo oluwaṣeun ti a bi ni ojo kejila osu kefa odun 1988 je asare ori ọdán omo orile-ede Naijiria ti o ti jawe olubori gba awon ami-eye irisrisi nibi idije ere sísá ori ọdán fun orile-ede Naijiria .. | wikipedia | yo |
Ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ Wúrà fún ìdíje 4 × 100 nínú ìdíje 2015 African Junior Athletics Championships .Iṣẹ́ rẹ̀ ó ti kópa nínú ìdíje tí àwọn ọ̀jẹ̀ wẹ́wẹ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ọjọ́ orí wọn kò ju ọdún méjìdínlógún lọ tí ó 2014 wáyé ní ọdún (U18), tí ó sì gba ipò kẹta gba àmì-ẹ̀yẹ ''Bàbá’’ nínú ìdíje 100 (agbon), ní dédé àsìkò 12.57, tí àníeme Alphosus àti favor Ezie sì ṣíwájú rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Adam a Zang tí wọ́n tún mọ̀ sí Gwaska, jẹ́ òṣèré,olùgbéré-jáde, adarí eré, olùkọ̀tàn, olórin ọmọ ẹ̀yà Hausa ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni wọ́n gbà wípé ó jẹ́ ẹni tó lààmì-laaka jùlọ ní agb kannywood.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2019, ó júwe ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ẹni tí ó nípa jùlọ ní ilẹ̀ Hausa.. | wikipedia | yo |
Púpọ̀ nínú àwọn adarí eré ní àgbà Kanńyé ni wọ́n ń gbóríyìn fún látàrí bí ó ṣe lè kópa dáradára ní inú ipa èyíkèyí tí wọ́n bá fún wípé kí ó ṣe.. | wikipedia | yo |
Adamu zsvNGO ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bi ti Ali Nuhu náà ní agbo àwọn òṣèré kannywood.Igba Ewe àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Adam Abdullahi Zang ní inú Oṣù Kẹwàá ọdún 1985, ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Zang ní Ìpínlẹ̀ Kaduna.. | wikipedia | yo |
Zang ko lo si ile-eko giga kankan, amo o lero wipe odun ju ki a ko iwe-ẹri aowo lo, amo o lo si ile-eko alakoobere ni aarin odun 1989-1995, ti o si lo si ile-eko guRama ni àárí odun 1996-2001.Iṣẹ rẹ Adam Zang ti bere si n korin nigba ti o ti wa ni ile-eko girama .. | wikipedia | yo |
òun náà ló ma n ṣojú ilé-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní inú ìdíje eré àti orin ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Zangô dara pọ̀ mọ́ kanywood ní ọdún 2001gẹ́gẹ́ akọrin, àmọ́ tí ó lo àǹfàní yí láti bẹ̀rẹ̀ sí ń kópa nínú ẹ̀ae eré orí-ìtàgé gbogbo.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu eré tí ó ti tó ọgọrun un ṣaájú kí ó tó di agbá òjẹ òṣèré ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O ti gba ami-eye Africa Movie Award in London, ni ilu UK.Bí o se lo si ẹ̀wọ̀n won fi Ádám a.. | wikipedia | yo |
Zang sí ọgbà ẹ̀wọ̀n fún Bí ó ṣe lu òfin ikanian ní ti ọdún 2007 látàrí orin rẹ̀ tí ó gbé jáde lóri ètò ìnìyàn tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ BahaIMiyà.Iore Àánú Rabe inú oṣù kẹwàá ọdún 2019, Adam fún àwọn ọmọ aláìya ní Iye tí ó tó 47 million láti lè jẹ́ kí wọ́n tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ wọn.Àwọn àṣàyàn eré àkò Ìtọ́kasíìtàkùn ìjáHauv Ọjọ́ìbí ní 1985, Malelé Film Actors Mass Mass Mẹ́7VIànímọ́ Ènìyàn Alààyè From Cheama Misan In Hausa Cind- Century AC-U Àjàpá Actors | wikipedia | yo |
Memry Savanhu (tí a tún le kọ bíi Memory Savanhu ) jẹ́ òṣèré Nollywood ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Sìmbábúè, olùgbéré-jáde, àti olùṣòwò tí ó n gbé ní ìlú Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, lẹ́hìn tí ó kó kúrò ní ìlú Lọ́ndọ̀nù.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe àkọ́kọ́ ipa fíìmù rẹ̀ nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Distance Between ní ọdún 2008.. | wikipedia | yo |
O ti wa ṣe bẹẹ kopa ninu ọpọlọpọ awọn fiimu Nollywood lati igba naa to fi mọ One Fine Day, on Bended Knees ati '76.. | wikipedia | yo |
Òun ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ agbéréjáde kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Memkay Productions.ètò ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a gbọ́ wípé orílẹ̀-èdè Sìmbábúè ni wọ́n bí Savanhu sí, ó sì sọ di mímọ̀ pé ẹ̀yà Zuruuru ni òún jẹ́.. | wikipedia | yo |
Ó kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ eré ṣíṣe ní ìlú Lọ́ndọ̀nù àti ìmọ̀ fíìmù ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga New York Film Academy tí ó wà ní Abu Dhabi, UAE.Iṣẹ́ rẹ̀ Savanhu ṣe àgbéjáde àkọ́kọ́ fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ ń ṣe Distance Between ní ọdún 2008.. | wikipedia | yo |
Oludari ere naa ni Izu Ojukwu ti awon olukopa sii pelu Rita Dominic, Mercy Johnson, Kalu Ikeagwu ati Yemi Blaq.. | wikipedia | yo |
Lara awon ere re miran ti o gbe jade ni one Fine Day, Cougars Reloaded, Catwalq ati on Bended Knees.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó kópa gẹ́gẹ́ bi “Eunice” nínu eré Izu Ojukwu kan tító dá lóri ìtàn tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ‘76.. | wikipedia | yo |
Awon olùjọkopa re tun pelu Rita Dominic, Ramsey Nouah, Chidi Mokeme, Ibinabo Fiberesima ati Daniel K.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà jáde ní 3 Oṣù kọkànlá, Ọdún 2016.Ní ọdún 2014, wọ́n yàán fún àmì-ẹ̀yẹ "Best Actor UK Female" níbi ayẹyẹ Zulu African Academy Awards (ZAFAA), tí ó wáyé ní ìlú Lọ́ndọ̀nù fún ipa rẹ̀ nínu fíìmù Maria's Vision.. | wikipedia | yo |
Ugonna Uvrou jẹ́ òṣèrébìnrin àti aṣàpẹẹrẹ ohun-ẹ̀ṣọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni ó ní ilé-ìtajà aṣọ tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ House of Noodra.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn ÀAlààyèọdún Ọjọ́ìbí Kosi (àwọn ènìyàn Alààyè)Àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Regina Askia-Williams (tí àbísọ rẹ̀ n ṣe Imaobong Regina Askia Usoro) jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ń gbé ní Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìlera, Aṣètò fún ètò-ẹ̀kọ́, ònkọ̀tàn, àti sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ tí ó di ìlúmọ̀ọ́ká gẹ́gẹ́ bi òṣèré àti afẹwàṣiṣẹ́.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 1988, wọ́n dé Askia-Williams ládé Miss UNIG, gẹ́gẹ́ bí ọmọbìnrin tí ó rẹwà jùlọ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ìlú Èkó.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1988 kan náà, ó díje nínú ìdíje ẹ̀wà MBgn tí ó sì ṣe ipò kejì.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1990, Askia-Williams tún ṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà níbi ìdíje ẹwà Miss Charm International tí ó wáyé ní ÌlúLeningrad, orílẹ̀-èdè Rọ́sí tó sì tún ṣe ipò kejì.. | wikipedia | yo |
Òun ni ẹni àkọ́kọ́ tí yóó sojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà níbi ìdíje Miss International, èyí tí ó wáyé ní orílẹ̀-èdè Japanlẹ́hìn tí ó di gbajúmọ̀ ní Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bi oludije ẹwà, Askia-Williams bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe iṣẹ́ afẹwàṣiṣẹ́.. | wikipedia | yo |
Gẹ́gẹ́ bi afẹwàṣiṣẹ́, ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìpolówó ọjà lóri tẹlifíṣọ̀nù àti ìwé-ìròyìn fún àwọn ilé-iṣẹ́ àti ilé-ìtajà bíi kessingsheen, Colleblesbles àti Visine.. | wikipedia | yo |
Ni odun 2007 oun ati omo re Stephanie Hornecker dìjọ se ipolowo fun ile-iṣẹ 2000-n-six.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2005 o ṣeto ifihan kan ni Ilu New York, léte lati la àwọn ènìyàn lọ́yẹ̀ nípa àwọn iṣoro ti o doju kọ àwọn ohun-elo amayederun ni Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2006 bákan náà, ó tún ṣe ìfihàn míràn ní agbègbè Lehman College, ìlú New York láti ṣàfihàn iṣẹ́ àwọn aṣàpẹẹrẹ ilẹ̀ Áfríkà àti ti ilé-iṣẹ́ tirẹ̀ náà tí ó pè ní Reṣẹ́jú Fashions.Askia-Williams kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Fortunes ní ọdún 1993 gẹ́gẹ́ bi Tokunbo Johnson.. | wikipedia | yo |
Eré náà ṣokùn fa ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ipa tí ó padà kó nínu àwọn fíìmù Nollywood .. | wikipedia | yo |
TsemiTope Solaja ti gbogbo eniyan mo si '"star girl" jẹ́ òṣèrébìnrin, olùgbéré-jáde, ònkọ̀tàn ,oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .Igba ewe kòlé bí Tope ní ìlú Sagamu ní Ìpínlẹ̀ Ògùn.. | wikipedia | yo |
Òun ni àkọ́bí àwọn òbí rẹ̀, amo ìyá rẹ̀ ni ó tọ́ dàgbà látàrí ìpinyà tí ó dé bá ìgbéyàwó àwọn òbí rẹ̀.ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀Tope lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ "Obánì" tí ó wà ní ìlú Sagamu ní Ìpínlẹ̀ Ògùn.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti ikéne rẹ́mọ ní ìpínlẹ̀ Ògùn, níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí ìwé mẹ́wàá.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 20017, ó wọlé sí ilé-ẹ̀kọ́ Faṣiti Tai Solari láti kọ́ nípa ìmọ̀ Mass Communication.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèréTope bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe ní ọdún 2007, nígbà tí ó kópa nínú eré Bamitalé, eré tí àfẹ́èṣì Eniola gbé jáde.. | wikipedia | yo |
àfẹ́ẹ̀fẹ́z n ya apá kan eré yi ní inú ilé-ẹ̀kọ́ fásitì táì ààrin tí ó sì béèrè lọ́wọ́ àwọn olùwòran bí ẹnikẹ́ni bá nífẹ́ sí láti kópa gẹ́gẹ́ bí árugba kejì.. | wikipedia | yo |
Eniola àti ọ̀rẹ́ rẹ̀ ọ̀gbẹ́ni Ẹjalónibú pẹ̀lú gbajú-gbajà òṣèré Adébá Tijani ni wọ́n ṣe àyẹ̀wò fún tí ó sì yege.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí Tope bá wọn kópa níní eré yí gblẹ́gẹ́ bí árugba tán, ó padà lọ bá àfẹ́èṣìz Eniola láti dáraó mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré rẹ̀ lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ méjì.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀ síwájú láti máa ṣeré orí-ìtàgé Yorùbá títí ó fi jáde ilé-ẹ̀kọ́ rẹ̀, àmọ́ èyí ṣe àkóbá fún ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ tí ó sì jẹ́ kí ọdún jàn ó tún orí ọdún tí ó yẹ kí ó jáde ẹ̀kọ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu eré tí ó ti tó inú eré Yorùbá nìkan ni ó ti ma n kópa, amo ó kópa nínu eré Gẹ̀ẹ́sì lẹ́ẹ̀kan, eré tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ The Antuque.. | wikipedia | yo |
Eré tí D.J tẹ̀ẹ́ kò tí dárasen Richards sì gbé jáde.Tope náà kọ eré tirẹ̀ tí ó pè ní árugbà tí gbájúmọ́ òṣèré Suz Lníyàn darí rẹ̀ ní ọdún 2015.Ó tún gbé eré Ashabi Akata jáde ní ọdún 2017, eré tí Ibrahim Yẹkini darí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Eré yí ní Azẹ̀ẹ̀] soronmu ko, ti àwọn òṣèré bi Bimbo ọsin niyì Jhonson àti Jùmọ̀kẹ́ George ti kópagbolájà Ghe bi oniṣowo ni ó ni ile-itaja aṣọ Star Girl luxury Store.Awon Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi atọ́kùn ètò tẹlifíṣọ̀nù kan táa pè ní 53 Extra, èyí tí ó maá n jẹ́ gbígbé sáfẹ́fẹ́ lóri ìkànnì Africa Magic .Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Edewor àti ìkejì rẹ̀ Kessiana ní ilé-ìwòsàn Portland ní ìlú Lọ́ndọ̀nù.. | wikipedia | yo |
Ìyá rẹ̀ tí n ṣe Juliana Edewor jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ náà tí orúkọ rẹ̀ n ṣe Hugh Thorley, jẹ́ ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí Edewor kọrawọn sílẹ̀ nígbàtí ó wà lọ́mọdé, àwọn méjèjì sì tún ìgbéyàwó ṣe pẹ̀lú ẹlomiran.. | wikipedia | yo |
Ọkọ tí ìyá rẹ̀ padà fẹ́ ti di olóògbé.Edewor dàgbà ní Nàìjíríà àti Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Ó gbé ní ìlú Èkó títí ó fi pé ọmọ ọdún mẹ́tàlá, níbi tí ó ti ní ètò-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ láti ilé-ìwé St.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn náà Edewor padà sí Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, níbi tí ó ti lọ sí ilé-ìwé Benenden School for Girls.Edewor gba oyè-ẹ̀kọ́ ní ọdún 2008 nínu ìmọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì àti eré ìtàgé láti Warwick University tó wà ní ìlú Coventry.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn náà, ó kẹ́kọ̀ọ́ eré fíìmù ṣíṣe fún Oṣù mẹ́ta ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga New York Film Academy ní ọdún 2009.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ Edward kọ́kọ́ ṣàfihàn nínu tẹlifíṣọ̀nù ní ọdún 2006 nígbà tí ó fi díje níbi Britain's Next Top Model.. | wikipedia | yo |
ó kópa nínú àwọn sinimá àgbéléwò ní àkókò ìgbà tí ó n kàwé lọ́wọ́.Ó kópa nínú fiimu ọdún 2010 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Sex & Drugs & Rock & Roll.Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1986àwọn ènìyàn alààyèàwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Vitalina Varela (tí wọ́n bí ní ọdún 1966) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Cape Verde.Isẹ̀mí rẹ̀ wọ́n bí Varela ní orílẹ̀-èdè Cape Verde.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Joaquin Varela ní àwọn ọdún 1980, wọ́n sì ti ní àwọn ọmọ méjì.. | wikipedia | yo |
Varela kó àkọ́kọ́ ipa fíìmù rẹ̀ ní ọdún 2014 nínu eré kan tí Pedro Costa ṣe tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Horse Money.. | wikipedia | yo |
Varela kìí ṣe iṣẹ́ òṣèré tẹ́lẹ̀ bẹ́ẹ̀ si ni kò kọ́ṣẹ́ eré ṣíṣe.. | wikipedia | yo |
Ṣugbọn lẹhin ti oun ati Pedro Costa di ọ̀rẹ́ nipasẹ fiimu ti wọ́n di jọ ṣiṣẹ́ pọ̀ lórí rẹ̀, Costa wòye pé ó yẹ ki àwọn ṣe fiimu míràn lórúkọ rẹ̀.Ni ọdún 2019, ó kópa nínú eré tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Vitalina Varela, tí Costa sì jẹ́ olùdarí.. | wikipedia | yo |
Ipa rẹ̀ dá lórí fífẹ arákùnrin kan gẹ́gẹ́ bí ọkọ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Arákùnrin náà di ẹni tí wọ́n wá fún bí ogójì ọdún tí àwọn méjèjì síì kọ láti fojú títí arákùnrin náà fi jẹ́ Ọlọ́run nípè.eré náà dá lóri ìṣẹ̀lẹ̀ ayé Varela fúnwá, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe jẹ́ wípé lẹ́hìn ọjọ́ kẹẹ̀ta ti ọkọ rẹ̀ ṣaláìsí ni ó wá lọ sí ìlú Lisbon.. | wikipedia | yo |
Peter Braìrẹ̀wẹ̀sì fi ẹ̀yin fún Varela fún iṣẹ́ takuntakun rẹ̀ nínú eré náà.. | wikipedia | yo |
Corine Onyango (tí wọ́n bí ní ọdún 1984/1985 ) jẹ́ òṣèrébìnrin àti atọ́kùn ètò orí rédíò ọmọ orílẹ̀-èdè Kẹ́nyàì rẹ̀ wọ́n bí Onyango ní orílẹ̀-èdè Kẹ́nyà.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ ilé ìfowópamọ́ tí ó wà fún ìdàgbàsókè ilẹ̀ Áfríkà, African Development Bank.. | wikipedia | yo |
Ó ti lo àwọn ìgbà ayé rẹ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè bíi Kenya, Ivory Coast, Tùnísíà, Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, Sìmbábúè àti Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Onyango gba oye-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Northwestern University ní ọdún 2007.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ipari ẹkọ rẹ, o pada si Kenya pẹlu ipinnu lati wa lo akoko ìsimi rẹ nibẹ, ṣugbọn o yi ẹrọ rẹ pada ipinlẹ to si pinnu lati fi Kenya ṣe ibùgbé.. | wikipedia | yo |
Onyango gba iṣẹ́ atọ́kùn ètò rédíò ní ilé-iṣẹ́ HomeBoy Radio.. | wikipedia | yo |
Onyango ṣàpèjúwe iṣẹ́ náà gẹ́gẹ́ bi ẹ̀kọ́ fún òun àti fún ilé-iṣẹ́ náà fúnpẹ̀lúní ọdún 2008, Onyango ṣe àkọ́kọ́ ipa fíìmù rẹ̀ nínu eré Wanuri Kahiu kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ From a Whisper.. | wikipedia | yo |
Ó kópa gẹ́gẹ́ bí Tamánì, ọmọbìnrin kan tí ìyá rẹ̀ ṣaláìsí ní àkókò ìṣemílòfo kan tí ó wáyé ní ìlú Nairobi ní ọdún 1998.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yan Onyango fún àmì-ẹ̀yẹ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, Onyango tún kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí ó wà fún àwọn ọmọde tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Tinga Tinga Tales.Onyango ti bí ọmọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ n ṣe King Kipa.. | wikipedia | yo |
Lily Banda (tí wọ́n bí ní 16 Oṣù Kẹẹ̀jọ, Ọdún 1990) jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Mawìmọ́tọ̀ rẹ̀ Banda jẹ́ ẹni tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ní ìfẹ́ sí orin kíkọ láti ìgbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rin.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí yóó fi pé ọmọ ọdún mẹ́fà, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kọrin níbi àwọn ayẹyẹ ní ilé-ìwé rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Banda bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2010 gẹ́gẹ́ òṣìṣẹ́ rédíò àti tẹlifíṣọ̀nù.. | wikipedia | yo |
Ṣugbọn ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀ lábẹ́ lílo Alex gẹ́gẹ́ bí orúkọ Ìdí-iṣẹ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Banda gbé akoko apapo awon orin re jade ni osu kini odun 2014.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, ó yí orúkọ ìdí-iṣẹ́ rẹ̀ padà sí Lily, èyítí ń ṣe orúkọ àbísọ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti African Union kan ní ọdún 2015, ó sì tún rí yíyàn fún àwọn àmì-ẹ̀yẹ ti AFRIMA ní ọdún 2018.Ní ọdún 2019, ó kọ orin àdákọ kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Bad at Love" | wikipedia | yo |
Wọ́n túmọ̀ orin náà sí èdè Swahili tó sì jẹ́ gbígbé jáde ní oṣù kíní ọdún 2020.. | wikipedia | yo |
Banda ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú Alfred Ochieng àti Aliza Were láti túmọ̀ orin náà.Ní ọdún 2019, Banda kópa nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Boy Who Harnessed the Wind, èyítí ó dá lóri Àkọsílẹ̀ William Kamkwa.. | wikipedia | yo |
Ó tún kópa gẹ́gẹ́ bi Aïcha Konate nínu abala ẹ̀kejì tí eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Deep State ní ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Ó kópa gẹ́gẹ́ bi atúmọ̀-èdè ọmọ orílẹ̀-èdè Mali kan tí àwọn kan gbìmọ̀ láti dáa lọ́nà àti láti ṣẹ́ku pàá.Banda máa ń rí ara fún àwọn ètò àwọn obìnrin.. | wikipedia | yo |
Warona Masego Setshwaelo (tí wọ́n bí ní ọdún 1976/1977 ) jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú fíìmù ọmọ orílẹ̀-èdè Bòtsmi rẹ̀ wọ́n bí Setshwaelo ní ìlú GBorone, orílẹ̀-èdè Botswana, ṣùgbọ́n ó lo àwọn ìgbà ayé rẹ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè bíi Ethiópíà, Swaziland, Gúúsù Áfríkà, àti Bòts | wikipedia | yo |
Ìyá rẹ̀ jẹ́ onímọ̀-ìjìnlẹ̀ nípa ìhùwàsí àwọn ènìyàn, bàbá rẹ̀ síì jẹ́ olóṣèlú tí orúkọ rẹ̀ ń ṣe Ephraim Setshwaelo.. | wikipedia | yo |
Setshwaelo lọ sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láti kàwé ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Virginia Tech.. | wikipedia | yo |
Setshwaelo jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n kọ́kọ́ kópa nínú ètò Big Brother Africa ní ọdún 2003, ó síì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n fìdí rẹmi nígbẹ̀yìn níbi ètò náà.Ní ọdún 2007, Setshwaelo kó lọ sí ìlú Montreal láti tẹ̀síwájú nínú iṣẹ́ òṣèré rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ère tó fi mọ́ NutMe Princess àti New Canadian Kid.. | wikipedia | yo |
Ó ní ipa kékeré kan nínu fíìmù ti ọdún 2013 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ White House Down.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, Setshwaelo kópa nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Waiting Room, èyí tí wọ́n ṣe ní ilé-ìṣeré Tarragon Theatre ní ìlú Toronto.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kẹẹ̀wá ọdún 2015, ó kópa gẹ́gẹ́ bi Odette nínu eré State of Denial.. | wikipedia | yo |
Setshwaelo tún kópa nínu Quantico ní ọdún 2016, àti ní ọdún 2018, nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ On the Basira of Sex.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2019, ó kópa gẹ́gẹ́ bí ìyá òṣìṣẹ́ agbófinró kan ti ń ṣe Lila Hines nínú eré Bang Bang.Ó fẹ́ràn kí ó ma dáná oúnjẹ àti kí ó máa ka ìwé.. | wikipedia | yo |
Joelle Kayembe Hagen (tí wọ́n bí ní 31 Oṣù Kaàrún, Ọdún 1983) jẹ́ afẹwàṣiṣẹ́ àti òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Kóngò.Itọ̀ rẹ̀ wọ́n bí Kayembe ní ìlú Lubumba, ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ olùṣòwò kan ní ilẹ̀ Kóngò tí orúkọ rẹ̀ n ṣe Kalonji Kayembe.. | wikipedia | yo |
Kayembe jẹ́ àkọ́kọ́ obìnrin Adugbọ̀n tí yóó hàn nínu ìwé ìròyìn Sports Illustrated .. | wikipedia | yo |
O tun han ninu ọpọlọpọ awọn iwe iroyin miran bii Cosmepolitan ati elle, ati fun ti ipolowo ọja kan ti o ṣe fun Sprite Zero.. | wikipedia | yo |
Kayembe kópa níbi àṣekágbá ìdíje International Supermodel ti ọdún 2005 tí ó wáyé ní orílẹ̀-èdè Ṣáínà.Ní Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹẹ̀sán Ọdún 2008, Kayembe ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú Bongani Mwanewane.. | wikipedia | yo |
Ṣugbọn latari awon ede-Aiye kan ti o si yo laarin won, ile-ejo kan paa láṣẹ fun won lati pínpin ni osu kinni odun 2011.Kayembe ko ipa Zina ninu fiimu Jérôme Salle kan ti odun 2013 ti akole re je Zulu.Ni odun 2015, Kayembe ṣiṣẹ́ pelu Trace Foundation lati pese awon ohun-Ìkẹ́kọ̀ọ́ fun awon ọdọmọbinrin meji kan.. | wikipedia | yo |