cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Amelia Umuhire (tí wọ́n bí ní ọdún 1991) jẹ́ olùdarí eré, agbéréjáde, àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Rùwándà àti Jẹ́mánì.Itọ̀ rẹ̀ Umuhire ní ẹni tí wọ́n bí ní ìlú Kìgálì, orílẹ̀-èdè Rùwándà ní ọdún 1991.. | wikipedia | yo |
Ó ní àwọn ọmọìyá méjì méjì kan tí wọ́n ṣe Anna Dushime àti Amanda Mukasonga.. | wikipedia | yo |
Ìyá rẹ̀ tí n ṣe Esther Mujawàyó jẹ́ Ajìjàgbara àti oniwosan.. | wikipedia | yo |
Ni akoko ipa-ẹya-run ti o waye ni orile-ede Rùwáńdà ni ọdun 1994, wọn ṣeku pa baba rẹ ati anti rẹ ti wọn jẹ ẹya Tutsi.. | wikipedia | yo |
Wọ́n gbé Umuhire sá lọ sí orílẹ̀-èdè Jemani níbi tí ó ti lọ àwọn ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ tí wọ́n sì fún ní ànfàní láti di ọmọ-ìfi.. | wikipedia | yo |
Umuhire ka àwọn ìwé rẹ̀ ní ìlú Vienna àti ní ìlú Berlin.Ní ọdún 2015, ó ṣe adarí eré fún ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀ pẹ̀lú dídarí eré Polyglot .. | wikipedia | yo |
Umuhire tún ti darí fíìmù oníṣókí kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Mujamila ní ọdún 2016.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣètò fíìmù náà ní ìlú Kìgálì, ó síì dá lóri ẹnìkan tí ó ṣe àbẹ̀wò sí orílẹ̀-èdè Rùwándà fún ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀ láti ìgbà ipa-ẹ̀yà-rún ti ọdún 1994.. | wikipedia | yo |
Òun náà ló ṣe adarí fídíò kan tí wọ́n lò níbi ayẹyẹ àjọ̀dún tí the miṣéducation of Lauryn Hill... | wikipedia | yo |
Susan Basemera jẹ́ akọrin àti òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Uganda.Isẹ̀mí rẹ̀ Basemera bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ lọ́mọ ọdún mẹ́jọ ní ìgbà tí ó fi wà nínu ẹgbẹ́ akọrin ti ilé-ìwé rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ nígbà tí ó fi darapọ̀ mọ́ àwọn ẹgbẹ́ akọrin kan tí wọ́n pè ní Waka Waka àti pẹ̀lú ṣíṣe orin tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní "Yimiimi àwo" ní ọdún 1995.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, Basemera lọ sí Amẹ́ríkà láti tẹ̀síwájú nídi iṣẹ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Bótilẹ̀jẹ́pé ó ti gbájúmọ́ ṣíṣe eré ìtàgé, ó tún gbé orin kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Goolo Goolo" jáde ní ọdún 2015.ní ọdún 2016, Basemera kópa nínu eré oníṣókí kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Gubaòǹṣèwéko ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Mamasrs Ali.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2020, Basemera kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Little America, eré tí ó dá lóri àwọn àtíkàn-wáwá ilẹ̀ Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Gentille Menguizani Assih (tí wọ́n bí ní 2 Oṣù Kẹẹ̀rin, Ọdún 1979) jẹ́ olùdarí eré àti agbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Togo.Itọ̀ rẹ̀ wọ́n bí Assih ní ìlú Kọ̀wọ́nme, orílẹ̀-èdè Tógò ní ọdún 1979.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2001, ó kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà àti fọ́tòyíyà | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2006, Assih tún kẹ́kọ̀ọ́ ìtàn-eré kíkọ ní orílẹ̀-èdè Sẹ́nẹ́gàl.. | wikipedia | yo |
Nígbà yìí kan náà ni ó gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga African Institute of Commercial Studies Ní ọdún 2009, Assih gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ ìṣàkóso àwọn òṣìṣẹ́.Assih ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ kan tó ń risi Bíbáraẹnisọ̀rọ̀ fún ọdún méjì ṣáájú kí ó tó dá ilé-iṣẹ́ tirẹ̀ sílẹ̀ tí ó pe orúkọ rẹ̀ ní “World Films” | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi olùdarí eré ní ọdún 2004 pẹ̀lú ṣíṣe àwọn fíìmù oníṣókí kan tí àkọ́lé wọn jẹ́ Le Prix du velo àti La vendeuse contaminée.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2008, ó ṣe adarí eré Itchombi.Ní ọdún tí ó tẹ̀le, Assih ṣe adarí àti agbéréjáde fún fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Bidenam, L'espoir d'un village ní ìlú Johannesburg, pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ ẹgbẹ́ Goethe Institute.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà dá lóri ayé Bidenam, ẹnití ó padà sí abúlé rẹ̀ lẹ́hìn ọdún mẹ́fà tí ó ti wà lááá, tó sì pinnu láti kọ́ àwọn ẹbí rẹ̀ bí wọ́n ti ń ṣe ètò ọ̀gbìn ní ìlànà ìbomirin.. | wikipedia | yo |
Àbúrò rẹ̀ obìnrin tí ó lọ kẹ́kọ̀ọ́ ní orílẹ̀-èdè Mòrókò ni ó mú àbá ìtàn ère náà wá.. | wikipedia | yo |
Gentille Assih at the Internet Movie Databaseàwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1979.. | wikipedia | yo |
Jacqueline Wolper Massawe (tí wọ́n bí ní 6 Oṣù kejìlá, Ọdún 1987) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Tànsáníài rẹ̀ Wolper lẹni tí wọ́n bí tó sì dàgbà ní ìlú Moshi, orílẹ̀-èdè Tànsáníà.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí Mawen Primary School fún ètò-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ṣaájú kí ó tó lọ sí àwọn ilé-ìwé bíi Magrath, Enywa àti Masai fún ètò-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Wolper ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù tí ó gbajúmọ̀ tó fi mọ́ Tom Boy - Dike Dume, Crazy desire, Mahaba Niue, I am not your Brother, Chaguo Langu, Dereva Taxi, Shoga Yangu, Red Valentine àti Family Tears.. | wikipedia | yo |
Àwọn ará Kenya fìyìn fún Wolper fún àwọn ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré Red Valentine àti Family Tears, èyí tí ó mú kí ó di ọ̀kan lára àwọn òṣèrébìnrin tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní Tànsáníà.. | wikipedia | yo |
Yato si iṣẹ ere sise, Wolper je oludasile ile-itaja Houseẹ̀sanstylishtz, ile-itaja aṣọ kan ti o wa ni ilu Dar es Salaam.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2018, wọ́n yan Wolper sí ara àwọn ìgbìmọ̀-adájọ́ níbi ìdíje Miss Tanzania, ṣùgbọ́n wọ́n padà yọ orúkọ rẹ̀ kúrò lẹ́hìn tí ó pẹ́ dé ibi àpèjọ ní.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ Wolper bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe wọléwọ̀de pẹ̀lú akọrin kan tí wọ́n pè ní Harmonize ní Oṣù Kaàrún Ọdún 2016, ṣùgbọ́n àwọn méjèjì pínyà ní Oṣù Kejì, Ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
Bótilẹ̀jẹ́pé ó ní ìfẹ́ sí àṣà ilẹ̀ Kẹ́nyà, Wolper sọ di mímọ̀ wípé òun kò lè ṣe wọléwọ̀de pẹ̀lú okùnrin ará Kẹ́nyà.Ní ọdún 2018, ó kéde pé òun ti di ìbí.àwọn Ìtọ́kasíàwọn ànilén ìjáde Jacqueline Wolper at the Internet Movie Movieàwọn ènìyàn tíáàwọn Ọjọ́ìbí ní 1987.. | wikipedia | yo |
Chloé Aïcha Boro Letterier (tí wọ́n bí ní 24 Oṣù Kaàrún Ọdún 1978) jẹ́ olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Bùrkínà Fasọ̀.I rẹ̀ Boro dàgbà ní ìlú Ouagadougou nítòsí Balolé Quarry.. | wikipedia | yo |
Ó kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ nípa àwọn Àkọsílẹ̀ ti ìgbàlódé, ó sì lépa ṣíṣe iṣẹ́ agbéròyìn.. | wikipedia | yo |
Ó ti kọ́ àwọn àyọkà fún àwọn ilé-iṣẹ́ oníròyìn bíi “La Vox Duix Dura àti “Le Marabout", ó sì ṣe àtẹ̀jáde àkọ́kọ́ ìwé-ìtàn rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ paroles orpheline ní ọdún 2006.. | wikipedia | yo |
Boro padà gbájúmọ́ ṣíṣe iṣẹ́ fíìmù, tó sì ṣe igbákejì adarí àti atọ́kùn ètò tẹlifíṣọ̀nù kan tí wọ́n pè ní Koodo, èyítí ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Galian ní ọdún 2006.. | wikipedia | yo |
O tun ṣe atọkun eto redio kan fun ikanni Radio Gammbidi.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, Boro kó lọ sí orílẹ̀-èdè Fránsì.Ní ọdún 2012, ó darí fíìmù fún ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀ pẹ̀lú dídarí fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Sur les traces de Salimata .. | wikipedia | yo |
Boro tún ṣe àkọ́kọ́ fíìmù gígùn oníìrírí-ayé tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Farafin kọ ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, ó ṣe adarí eré France-Aurevoir, le nouveau Commerce triangulaire .. | wikipedia | yo |
Eré náà gba àmì-ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bi fíìmù ìrírí-ayé tí ó tayọ jùlọ níbi ayẹyẹ Festival International de cinema Vues d'Afrique, èyí tí ó wáyé ní ìlú Montreal.. | wikipedia | yo |
ní ọdún 2018, Boro kọ ìwé-ìtàn kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Notre ddd Interi€, èyítí ó n sọ ìtàn nípa ẹnìkan tí ó padà sí abúlé rẹ̀ tí ó wà ní ilẹ̀ Áfríkà láti orílẹ̀-èdè Fránsì.. | wikipedia | yo |
Boro ṣe adarí eré ìrírí-ayé tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Le LoUp D'Or de Balolé ní ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Eré náà dá lóri ìfipáyí ètò ìṣèjọba tí ó wáyé ní ọdún 2014 àti àwọn ipa tí ó là lára àwọn òṣìṣẹ́ Balolé Quarry.. | wikipedia | yo |
Bella Awa Gassama jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Gábíàbíàbíà.I rẹ̀ Gassama ní ìbátan pẹ̀lú oníìdájọ́ bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ti ń ṣe Bakary "Pápá Gassama.. | wikipedia | yo |
Ó parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní ilé-ìwé Marina International School ní ọdún 2004.. | wikipedia | yo |
Ó kó àkọ́kọ́ ipa rẹ̀ nínu fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Arrou ní ọdún 2004 yìí kan náà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n wo fíìmù náà níbi ayẹyẹ Pan-African Film Festival kan tí ó wáyé ní ìlú Los Angeles, Gassama náà sì tún rí yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ 2nd Africa Movie Academy Awards.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún yàán fún òṣèré ilẹ̀ Gábíàbíà tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ Inshasha Film Festival.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2008 bákan náà, Gassama tún kó àkọ́kọ́ ipa rẹ̀ nínu fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ My Gammbian káwọn pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Desmond Elliot àti Oge Okoye.. | wikipedia | yo |
Ó tún kó ipa amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ nínu fíìmù Mirror Boy ti ọdún 2011, ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Fatima Jambbe àti Genevieve Nnaji.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, Gassama parí ìkẹ́kọ̀ọ́ láti ilé-ẹ̀kọ́ gígaTask crown College.Gassama kópa nínu eré Siting Diallo kan ti ọdún 2014 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Soul.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yàán fún àmì-ẹ̀yẹ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ Zulu African Film Academy Awards.. | wikipedia | yo |
Ó kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù ti ọdún 2019 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ NKala.. | wikipedia | yo |
Theresa Traoré Dahlberg (tí wọ́n bí ní 1 Oṣù kọkànlá Ọdún 1983) jẹ́ olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Swídìn àti Bùrkínà Fasọ̀iṣẹ́ rẹ̀ Dahlberg jẹ́ ọmọ sí akọrin ilẹ̀ Bùrkínà Fasọ̀ kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Richard Seydou Traoré.. | wikipedia | yo |
Ó dàgbà ní Bùrkínà Fasọ̀ àti ní ìlú Öland tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Swídìn.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí rẹ̀ ṣiṣẹ́ fún Àjọ Àgbáyé fún ètò ìsókè ní orílẹ̀-èdè Bùrkínà Fasọ̀.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn tí Dahlberg parí ilé-ìwé girama rẹ̀, ó kó lọ sí ìlú New York ní orílẹ̀-èdè ìhùkòrí Amẹ́ríkà, níbi tí ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn iṣẹ́ tó fi mọ́ èyí tí ó ṣe nínú ọgbà ìṣeré kan.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2007, ó forúkọsílẹ̀ ní ilé-ìwé The New School tí ó wà ní ìlú New York.. | wikipedia | yo |
Dahlberg gba oyè-ẹ̀kọ́ láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Stockholm Academy of Dramatic Arts, bẹ́ẹ̀ ló sì tún gba oyè gíga nínu ìmọ̀ Fine Arts láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Royal Academy of Arts.Dahlberg darí àkọ́kọ́ fíìmù oníṣókí rẹ̀ ní ọdún 2006.. | wikipedia | yo |
Ó tún ṣe àgbéjáde eré ọgbọ̀n-ìṣẹ́jú kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ On Hold ní ọdún 2009.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn náà, Dahlberg ṣiṣẹ́ fún àwọn ètò tẹlifíṣọ̀nù ti Swídìn, ó sì darí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2011, ó ṣe adarí eré ìrírí oníṣókí kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Taxi Sisters, èyí tí ó dá lóri àwọn obìnrin awakọ̀ kábubu ní orílẹ̀-èdè Sẹ́nẹ́gàl.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, Dahlberg darí eré gígùn tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ oúaga Girls.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà dá lóri àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin ilẹ̀ Bùrkínà Fasọ̀ tí wọ́n ti yàn láti máa ṣiṣẹ́ atọ́kọ̀ṣe.. | wikipedia | yo |
Eré náà ṣàfihàn ìgbésí ayé wọn ní ìgbà tí wọ́n wà ní ilé-ìwé àti lẹ́hìn tí wọ́n jáde ilé-ìwé, ó sì ṣàlàyé àwọn ìdí tó mú kí wọ́n yàn láti máa ṣe irú iṣẹ́ bẹ́ẹ̀ - àwọn kan nínú wọn ti pàdánù àwọn òbí wọn, bẹ́ẹ̀ làwọn míràn síì ti lọ ní oyún ẹlẹ́yà nígbà tí wọ́n ń dàgbà bọ̀.. | wikipedia | yo |
oúàga girls gba ami-eye ti CDIFF nibi ayeye Carthage Film Days.. | wikipedia | yo |
Dahlberg darí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Ambassador's Wife ní ọdún 2018.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà gba àmì-ẹ̀yẹ Tempo Documentary Short Award, tí Dahlberg náà fún síì gba àmì-ẹ̀yẹ ti Bekers Art Award ní ọdún 2019.yàtọ̀ sí ṣíṣe iṣẹ́ fíìmù, Dahlberg tún maá n ṣiṣẹ́ agbẹ́gilére.. | wikipedia | yo |
Marina Niava (tí wọ́n bí ní ọdún 1985) jẹ́ olùdarí eré, agbéréjáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Côte d'Ivoire.Isẹ̀mí rẹ̀ Niava ni àbígbẹ̀yìn àwọn òbí rẹ̀ tí wọ́n ṣe Pierre àti Cécile Niava.. | wikipedia | yo |
Ó gba oyè-ẹ̀kọ́ láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Lycée Sainte Marie d'Abidjan, tó sì tún gba àmì-ẹ̀yẹ series a Excellence Award fún píparí ẹ̀kọ́ rẹ̀ lọ́nà tó peregedé.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn tí ó gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ Ìgbéròyìn láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Institut des Sciences et Techniques de la Communication, Niava gbégbá orókè níbi ìdíje kan tí ilé-iṣẹ́ Radio Jam ṣe ní ìlú Abidjan.. | wikipedia | yo |
Niava bẹ̀rẹ̀ sí ní ní ìfẹ́ sí iṣẹ́ sinimá nígbà kan tí ó fi ṣiṣẹ́ lóri ìpolówó ọjà kan.Láti ọdún 2009 sí 2010, Niava ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́bi ònkọ̀tàn fún abala àkọ́kọ́ ti eré tẹlifíṣọ̀nù alátìgbà-dègbà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Teenager, èyítí ó gba àmì-ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bi eré alátìgbà-dègbà tí ó dára jùlọ ní ilẹ̀ Áfríkà níbi ayẹyẹVues d'Afrique Festival tí ó wáyé ní ìlú Montreal.. | wikipedia | yo |
Ó kó lọ sí ìlú Oslo, ní orílẹ̀-èdè Nooriywe ní ọdún 2010 tó sì di ọ̀gá ní ẹ̀ka ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ti ilé-iṣẹ́ African Cultural Center.. | wikipedia | yo |
Niava ṣe aláwole àjọ̀dún KinKin Afrika Film Festivals ti ọdún 2010 àti 2011 ní ìlú Oslo.. | wikipedia | yo |
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ níbi ètò Bẹnihàn International Foundation's Excellent scholarship program ní ọdún 2012.ní Oṣù Kẹẹ̀wá ọdún 2012, ó ṣe adarí fíìmù ìrírí fún ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àkọ́lé Fíìmù náà ní Noirs Au Soilil Lelé, èyí tí ó dá lóri ìgbésí ayé àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ilẹ̀ Áfríkà ní ìlú TsuKuba, orílẹ̀-èdè Japan.. | wikipedia | yo |
Àkọ́kọ́ fíìmù àròṣe rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ 21 jáde ní Oṣù kejìlá ọdún 2013.. | wikipedia | yo |
Ààjọ kan tí wọ́n pè ní Organisation internationale de la Francophonie ló ṣe onígbọ̀wọ́ fíìmù náà.. | wikipedia | yo |
Niava tún ṣe adarí eré táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní Worse ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Ó tún ṣiṣẹ́ lóri fíìmù ọdún 2015 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Advantage.Niava gba oyè gíga nínu ìmọ̀ nípa fíìmù àti tẹlifíṣọ̀nù láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Academy of Art University.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, Niava kọ àkọ́kọ́ ìwé-ìtàn rẹ̀ tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní, American Dreamer.. | wikipedia | yo |
Dyana Gaye (tí wọ́n bí ní ọdún 1975) jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Fránsì àti Sèdäse rẹ̀ wọ́n bí Gaye ní ìlú Paris, orílẹ̀-èdè Fránsì ní ọdún 1975.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ àwọn òbí tí wọ́n ti orílẹ̀-èdè Sẹ́nẹ́gàl wá sí Fráǹsì.. | wikipedia | yo |
Gaye kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ fíìmù ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga University of Paris 8 Vincennes-Saint-Denis.. | wikipedia | yo |
Ó gba ẹ̀bùn ìrànlọ́wọ́ kan láti ọwọ́ Louis Luere - Villa Medicis ní ọdún 1999 fún ìtàn-eré rẹ̀ tí ó kọ táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní Une meme pour Souleymane.. | wikipedia | yo |
Gaye náà ló ṣe adarí nígbà tí wọ́n fi n ṣiṣẹ́ láti gbé eré náà jáde ní ọdún 2000, eré náà síì gba àmì-ẹ̀yẹ níbi ayẹyẹ Dakar Film Festival.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2004, ó kópa níbi àṣeká ti ètò Rolex Mentor and Protége Arts Initiative.. | wikipedia | yo |
Gaye darí fíìmù oníṣókí kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ J'ai Deux amours ní ìlànà pẹ̀lú iṣẹ́ àkànṣe kan tí wọ́n pè ní Paris La métisse ní ọdún 2005.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún tí ó tẹ̀le, ó ṣe adarí fún ti eré Ousmane, èyítí wọ́n ṣe ní àṣeyege.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yàán eré náà fún àmì-ẹ̀yẹ eré oníṣókí tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ César Awards.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2009, Gaye tún ṣe olùgbéréjáde àti olùdarí eré aláwàdà kan tí a pe àkọ́lé rẹ̀ ní Saint Louis Blurs.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún yàán eré òun náà fún àmì-ẹ̀yẹ eré oníṣókí tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ César Awards bákan náà.. | wikipedia | yo |
Ààjọ kan tí wọ́n pè ní Focus Features Africa ni ó ṣe onígbọ̀wọ́ ètò náà.Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Gan Foundation Creation Prize ní ọdún 2012.. | wikipedia | yo |
Gaye darí fíìmù under the Starry Sky ní ọdún 2013, tó sì di àkọ́kọ́ fíìmù gígùn tí wọ́n gbéṣe ní ìlú Dakar, Turin, àti New York.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà jẹ́ wíwò níbi ayẹyẹ Toronto International Film Festival, ó sì tún gba àwọn àmì-ẹ̀yẹ méjì kan níbi ayẹyẹ Premiers Plans Angers Festival.. | wikipedia | yo |
Mereb Estifanos (tí wọ́n bí ní ọdún 1983) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Ẹritrẹ́à.Isẹ̀mí rẹ̀ wọ́n bí Estifanos ní ọdún 1983 ní ìlú Arareb.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ Estifanos Derar àti Negesti Wolde-Mariam.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe àpèjúwe ararẹ̀ pé òun gbajúmọ̀ ẹ̀kọ́ òun tí òun sì máa ń tara láti peregedé nínú ẹ̀kọ́ òun.. | wikipedia | yo |
Estifanos máa ń gbá bọ́ọ̀lù afowogba Volleyball ní ìgbà tí ó wà ní ilé-ìwé, ṣùgbọ́n ó dáwọ́ rẹ̀ dúró láti gbájúmọ́ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀.Bóbó Estifanos kọ́kọ́ fẹ́ láti di akọrin tàbí oníjọ́, ní ọdún 2002 ní Fesseh Lemlem, ẹni tí ó kọ ìtàn eré Ferleley, fi lọọ Estifanos láti wá kópa nínu fíìmù rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Nígbà náà, Estifanos síì wà ní ilé-ìwé girama kò sì tíì kó ipa eré kankan rí.. | wikipedia | yo |
Èyí mú kí ó máa ṣeyèméjì ṣáájú kí ó tó padà wá faramọ́ láti kópa nínú eré náà.. | wikipedia | yo |