cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Peters, tí ó wà ní Corin Camp ní ìpínlẹ̀ Enugu, nígbà tí ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní ìmanukwu grammer School ní ìpínlẹ̀ kan náà, ṣáájú kí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Fasiti ti ìlú Port Harcourt ní ìpínlẹ̀ Rivers..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ eré oníṣe, ó sì gboyè ẹlẹ́kejì nínú ìmọ̀ ìṣèlú ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ti Ìpínlẹ̀ Èkó.Òun àti ẹbí rẹ̀ ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Arábìnrin Cassandra Udokwu, tí wọ́n sì bímọ méjì fúnra wọn..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe lọ́dún 1967 níbí ìpàdé kan tí ó wáyé láàárín àwọn aṣojú olórí ìṣèjọba ológun ti ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti àwọn aṣojú olórí àwọn ènìyàn ní apá ìlà-oòrùn Nàìjíríà tí ajagun Colonel Odumegwu Ojukwu Darí..
wikipedia
yo
Wọ́n pe ìpàdé yìí láti wá ọ̀nà àbáyọ ìkẹyìn kí ogun abẹ́lé, Biafra máa bẹ́ sílẹ̀ nígbà náà..
wikipedia
yo
Yakubu Gowon- Ààrẹ Ológun Nàìjíríà Ọ̀gágun, lt.-
wikipedia
yo
Odumegwu Ojukwu – Gomina Ẹkùn ila Oorun NaijiriaỌ̀gágun, Major Mobolaji Johnson – Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó Ọ̀gágun, Tjìyà):
wikipedia
yo
Hassan Katwọ̀n – Gómìnà ẹkùn àríwá Ọ̀gágun, ltalagbalúgbú..
wikipedia
yo
David ẹjọ́or – Gómìnà ẹkùn àárín ìwọ̀ Oòrùn Ọ̀gágun, Commodọ̀rẹ́ Joseph Eobat Akinwale Wey – igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà Ọ̀gágun, Colonel Robert Adebayo – Gómìnà ẹkùn ìwọ̀ Oorun Alhaji Kam DuMMR..
wikipedia
yo
Akpan, akọ̀wé gómìnà ìjọba ológun ẹkùn ìlà oòrùn Nàìjíríà Alhaji Ali Akilú Akọ̀wé Gómìnà Ìjọba Ológun Ẹkùn Ariwa Naijiriad..
wikipedia
yo
Lawani under, akọ̀wé gómìnà ìjọba ológun ẹkùn àárín ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríàp..
wikipedia
yo
Oduṣumo, Akowe Gomina Ijoba ologun Ẹkun iwo Oorun Naijirias..
wikipedia
yo
Rodezua (eni ti o wa joba ni Ilu Benin, Ogbẹ̀sanlẹ i)àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Ebele Ooba Edomu© je òṣèrébìnrin àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríàigbe ayé àti ètò ẹ̀kọ́ kòlé bi òjíro ní ìlú Lọ́ndọ̀nù, wọ́n sì tó dàgbà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Ìpínlẹ̀ Ìpínlẹ̀ Ẹnú..
wikipedia
yo
O ti bẹrẹ si ni ṣere ori-itage lati igba ti o ti wa ni ile-ẹkọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ " Santa Maria Primary School"
wikipedia
yo
Tí ó sì tẹ̀ síwájú nínú eré rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ Nsukka's Queen of the Holy Rosary Secondary School..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó parí, ó wọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Calabar láti kọ́ nípa ìmọ̀ ìkọ́ni,..
wikipedia
yo
Okàrọ dara pọ̀ mọ́ àwọn elere oníṣẹ́ orí ìtàgé lẹ́yìn tí ó kàwé gboyè tán..
wikipedia
yo
Her Mother was a full-time Television producer and her father was an Engineer who had great interest in arts and literature.Iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn tí ó jáde fásitì tán, tí ó sì ṣe Agùnbánirọ̀ rẹ̀ tán ní ilé-iṣẹ́ Amóhùn-máwòrán NTA, ibẹ̀ ni ó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní Ifẹ̀ sí ṣíṣe iṣẹ́ lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán Bákan náà, ó ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ tí ó ń rí sí ìrìnà lọ sí òkè òkun ní ìpínlẹ̀ Èkó, ṣáájú kí ó tó padà sí ẹnu iṣẹ́ eré ṣíṣe.Ní ọdún 2014, Ebele ọká Edomu© gbé ère kan jáde tí ó pè ní Musical Whispers, èrè tí ó ke gbàjarè fún ìtọ́jú àwọn ọmọ tí wọ́n ní àìsànlẹ́hìn..
wikipedia
yo
It Features other prominent Nigerian Actors and Actresses, Most Notably Chioma Chukwuka and Kalu Ikeagwu.Látàrí eré yí, wọ́n fun ní alaje "Mama of Nollywood".Oun ati ebí rẹ̀ó lọ́kọ si ìdílé Edomu©àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ òun ni ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti African Magic Viewers Choice Awardin 2017, Her performance in 4–1 Love won Ọkàro the for Best Supporting Actress..
wikipedia
yo
She was Nominated for her rolei the movie 'SMS' at 2020 Africa Magic Viewers' Choice Awards for Best Actress in a Comedy (Movie/TV series).Awon aṣayan ere rẹàwọn itọkasiExternal linksáwọn eniyan Alààyè, Actresse(versity of Calabar Alumniyear of Birth Missing (Living People)Igbo Actresses..
wikipedia
yo
Mary nnena Njoku (bi ní Ọjọ́ Ogun, Oṣù Kẹta Ọdún 1985) jẹ́ òṣèré àti adarí fún ilé isẹ́ Rok Studios ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun ni o gbe ere thy Will Be Done ati Husband of Lagos jade, o si ṣe adari fun ere single Ladies ati Festac Town.ibẹrẹ pepe aye ati ẹkọ rẹ Mary Njoku jẹ ọmọ kẹfa ninu awọn ọmọ mẹjọ ti awọn obi rẹ bi..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Lagos State University níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Njoku darapọ mọ Nollywood ni ọdun 2003, nigba ti o wa ni ọmọ ọdun metadinlogun .Iṣẹ Njoku kopa ninu ere Home sickness ni ọdun 2004, eyi si ni ere ti o ma koko ṣe..
wikipedia
yo
Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó kópa nínu eré Blackberry Babes ní ọdún 2011..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2018, o gbe ere rẹ kale ti o pe ni Nwanyio.Ma. ayé rẹ Mary Njoku ṣe igbeyawo pẹlu Jason Njoku ni ọjọ kejidinlogun Oṣu Kẹjọ ọdun 2012..
wikipedia
yo
Makida kaka jẹ osere ati Rori ni orile ede Naijiria ti a bi si orile ede Egypt..ise ni odun 2015, o kopa ninu ere Code of Silence..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, ipa tí ó kó nínu eré taste of Love jẹ́ kí wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré tó dára jù lọ láti ọ̀dọ Nigerian Broadcasters Merit Awards..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017, ó kó ipa Melanie nínu eré Inspector K..
wikipedia
yo
Ó kópa nínu eré Banana Island Ghost GẸ́GẸ́ bi Indian níJa..
wikipedia
yo
O jẹ ambase fun ile ise Frankie and Co.Aṣayan awon ere ti o ti se Banana Island Ghost (2017) Code of Silence (2015) gidi Up (With OC ? taste of Love (with Blossom nínú Inspector) káwọn pọ̀..
wikipedia
yo
Mabel Akomu Oboh tí a mọ̀ sí Mabel Oboh tí wọ́n bí ní 18 Oṣù Kẹẹ̀rin, Ọdún 1964 jẹ́ òṣèrébìrin, atọ́kùn ètò orí tẹlifíṣọ̀nù àti agbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Òun ni olùdásílẹ̀ Mabel Oboh Centre for Save our Stars (MOCSOS)..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ àkọ́kọ́ ẹni tí yóó dánìkan gbé eré tẹlifíṣọ̀nù jáde pẹ̀lú eré rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Victims, tí ó jẹ́ gbígbé jáde lóri ìkànnì Nigerian Television Authority (NTA).Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ Mabel wá láti Ìpínlẹ̀ Ẹdó ṣùgbọ́n ìlú Èkó ni àwọn òbí rẹ̀ bi sí..
wikipedia
yo
Ó gboyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ nípa òràn dídá láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Bushire New University.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ Mabel bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ lágbo eré ìdárayá ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 1980..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ẹ̀kejì obìnrin tí yóó kọ́kọ́ dánìkan ṣe adarí eré àti olùgbéréjáde pẹ̀lú ṣíṣe eré rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Victims..
wikipedia
yo
Yóo gbalejo lórí ètò telifisonu pẹlu ètò ti akole re je "Chat with Mabel" tí wọ́n gbé sáfẹ́fẹ́ lóri ikanni NTA.O darapọ mọ́ ilé-ise NTA ní àwọn ọdún 1990 gẹ́gẹ́ bi olùgbéròyìn ṣaaju ki o to sise pelu aájò agbaye..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn náà ni ó darapọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ aṣojú Britani ní orílẹ̀-èdè Pólándì.Ò ṣíṣe rẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́, Mabel jẹ́ alagbasọ fún ẹgbẹ́ òṣèlú African Democratic Congress (AD.Ó gbégbá ìbò ní ọdún 2020 fún ti ètò ìdìbò Gómìnà Gómìnà Ẹdó.MOCSOS ó jẹ́ olùdásílẹ̀ Mabel Oboh Centre for Save our Stars (MOCSOS), léte láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ìlera àwọn òṣèré Nàìjíríà.Ọ̀rọ̀ ayé ara rẹ̀ ó ti bí àwọn ọmọkùnrin mẹ́ta, orúkọ ọkọ rẹ̀ náà náà sì ń ṣe Michael Nàìjíríà. Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1964 ní òṣèré ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Shafkat Bọ́sẹ̀ Adéìtìjú tí ó papọ̀ dá ní 23 Oṣù Kẹfà, Ọdún 2020 jẹ́ òṣèré Nollywood ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Madam Tinubu nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Efunroye Tinubu ..
wikipedia
yo
Ó tún ti kópa gẹ́gẹ́ bi “Mama Oni” pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Adebayo Salami nínu eré Fúnkẹ́ Akíndélé kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ọmọ ghetto.Bọ́sẹ̀ ṣaláìsí ní ọjọ́ kẹtàlélógún, Oṣù Kẹfà Ọdún 2020.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́lọ́lẹ ní 2020àwọn òṣèré ará Nàìjíríààwọn ọmọ Yorùbá..
wikipedia
yo
Chioma Omeruah, tí a mọ̀ orúkọ ìnagi rẹ̀ sí Chigul, jẹ́ apanilẹ́rìn-ín, akọrin, àti òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún àwọn ipa apanilẹ́rìn-ín rẹ̀ tí ó maá n sábà ṣe ní gbogbo ìgbàiṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí Omeruah sí ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Òun ni àbílé kejì nínú àwọn ọmọ mẹ́rin ti àwọn òbí rẹ̀..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ ni Samson Omeruah.Ó lọ sí ilé-ìwé girama méjì kan ní ìlú Jọs àti ní ìlú Ikeja, ó sì tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Ábíá fún Oṣù mẹ́ta, ṣááju kí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Delaware State University níbití ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ nípa òfin tó de àwọn ìwà òdarán..
wikipedia
yo
Nitori àìṣedẽdé rẹ̀ ninu ẹ̀kọ́ náà, ó padà tún kẹ́kọ̀ọ́ èdè Faransé lati ilé-ìwé Delaware State University bákan náà..
wikipedia
yo
Ó padà sí Nàìjíríà lẹ́hìn tí ó ti lo ọdún méjì ní ilẹ̀ Amẹ́ríkàó kọ́kọ́ di akọrin lábẹ orúkọ C-gígùn ṣùgbọ́n orúkọ Chigul bó ti tẹ́lẹ̀ mọ́lẹ̀ lẹ́hìn kíkó àwọn ipa apanilẹ́rìn-ín rẹ̀ nínu àwọn eré..
wikipedia
yo
Àkọ́lé àkọ́kọ́ orin rẹ̀ tí ó kọ ní "Kilode", èyí tí ó ṣe pẹ̀lú ìrúhùn rẹ̀ sílẹ̀ tí ó sì pín fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó ti kópa nínu eré Nollywood kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Road To Yesterday.Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀ Road to Yesterday (2015) The Wedding Party 2 (2017) Banana Island Ghost (2017) Chief 2003 (2018) The Ghost and the Tout (2018) charge and Bilta (2021)àwọn àmì-ẹ̀yẹ àti ÌFISỌRÍ Wori Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1976àwọn Ọmọ Igbó Alààyè Olúkúlùkù Ara Nàìjíríà ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Claire ẹ̀dùn, ti a mọ si oyinbo Princess, jẹ oṣere Nollywood ọmọ ile-Gẹẹsi..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún sísọ èdè píjìjì ti Nàìjíríà, èyí tí ó padà ṣokùn fa ipa tí ó kó nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Authentic Tentative Marriage (ATM) ní ọdún 2016, tí olùdarí eré náà n ṣe Lancelot Imasuen. rẹ̀ ẹ̀dùn ní ẹni tí a bí sí ọwọ́ àwọn òbí tí wọ́n jẹ́ ará Britani, ó sì ní ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ náà níbẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n nígbà tí ó fi rí iṣẹ́ kan gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ ọkọ̀ òfúrufú, èyí tí ó fun ní àǹfàní láti káàkiri àgbáyé, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní fẹ́ràn ilẹ̀ Áfríkà, pàápàá jùlọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó di ìlúmọ̀ọ́ká ní ọdún 2015 lẹ́hìn tí ó fi fídíò ara rẹ̀ hàn lóri ẹ̀rọ Ayárabíàṣá Faceebook níbi tí ó ti ń sọ èdè píjìnì ti Nàìjíríà pẹ̀lú ìṣírùn..
wikipedia
yo
Èyí ni olùdarí eré Lancelot Imasuen rí tí ó fi fún ní ipa nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ (ATM) Authentic Ten Marriage..
wikipedia
yo
Ó kó ipa gẹ́gẹ́ bi ọmọbìnrin ìjíṣe tí ó wá sí Nàìjíríà láti fẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tí ó n wá láti gbé ní ilẹ̀ Britani.àwọn eré tí ó ti kópa (ATM) Authentic Authentic Ten Marriage (2016)àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Ìgúnàwọn Ọjọ́ìbí ní 1985..
wikipedia
yo
Kehinde Fadipe (tí a bí ní 17 Oṣù Kẹfà, Ọdún 1983) jẹ́ òṣèrébìnrin ní Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì tí a bí sí ọwọ́ àwọn òbí tí n ṣe ará orílẹ̀-èdè Nàìjíríà rẹ̀ wọ́n bí Kehinde Fadipe ní ilé-ìwòsàn St Mary tí ó wà ní ìlú Lọ́ndọ̀nù ní ọdún 1983..
wikipedia
yo
O kọkọ gba oye-ẹkọ ninu imọ ede Gẹẹsi ṣaaju ki o to gba oye giga lati Royal Academy of Dramatic Art ni ọdun 2009.Akoko ipa rẹ ti o ṣe gboogi waye ni ọdun 2009 nigba ti o fi kopa ninu ere kan ti a pe akole rẹ ni Iluined, eyiti o gba ami-ẹyẹ ti Pulitzer..
wikipedia
yo
Telifisonu kan ti BBC gbe kalẹ̀ ti akọle rẹ jẹ The Body farm, eyi ti o da lori iwe kan ti Patricia Cornwell kọ ní ọdún 1994..
wikipedia
yo
Ó darapọ̀ mọ́ àwọn olùkópa lórí abala èkèeta eré Misfits níbití ó ti kópa gẹ́gẹ́ bí Melissa.Ní ọdún 2013, ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú wọlé Olufúnwa, èyí tí wọ́n ṣe fídíò rẹ̀ tí ìkànnì Channels TV Metrofile gbé sáfẹ́fẹ́..
wikipedia
yo
O ti ni àwọn ọmọ mejiàwọn itọkasi àwọn eniyan alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ni 1983àwọn ọmọ Yorùbá..
wikipedia
yo
Àgbọ́wá-Ìkòsì jẹ́ ìlú ṣèṣèṣè kan ní ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Lára ohun tó ṣe iyebíye nípa ìlú yìí ni pé; ojú-ọ̀nà wọn ló jẹ́ èkejì nínú àwọn ojú pópó tí wọ́n lo ọ̀dà tó dára jù láti fi tẹ́ ẹ.Ìtàn agbègbè kan tí wọ́n ń pè ní Ebàjẹ́ ní Àgbọ́wá-Ìkòsì ti ṣe wá..
wikipedia
yo
A pín ìlú náà sí àwọn agbègbè tó pọ̀, bíi;(ìtún); Aledo, Oríwú, Àgbọ́wá, Kòsọ́mi àti ẹ̀hìndi..
wikipedia
yo
Olórí ìtún ló ń ṣàkóso ọ̀kọ̀ọ̀kan nínú àwọn agbègbè wọ̀nyí, àti pé olórí ìlú gan-an ní agbègbè kọ̀ọ̀kan máa ń pe adarí wọn..
wikipedia
yo
Ìgbà tó yá ni wọ́n sọ ipò aṣáájú yìí di baálẹ̀ àti ọba..
wikipedia
yo
Lọ́dún 1956, Aláyélúwà, Ọba Edward Aláúsá Thomas OLÚWÀ ni wọ́n gbé adé lé lórí, gẹ́gẹ́ bíi Ọba àkọ́kọ́ nílùú Àgbọ́wá-Ìkòsì, láti agboolé Ogún-Olúwà-
wikipedia
yo
Àwọn agboolé marun-un ni wọ́n ṣàdéhùn pé àwọn yóo máa jọba nílùú ọ̀hún..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n Baálẹ̀ ló n ṣàkóóso àwọn ìgbèríko tó yí i ká, bíi; Ìkòsì, IGBENE, Oko-Ito, Òkè-Oli, Gbẹ̀rígbẹ̀, àtàwọn yóokù..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn baálẹ̀ náà ni wọ́n máa ń wáá jábọ̀ fún Ọba Àgbọ́wá-Ìkòsì, (ìyẹn Abọ́wá tìlúu Àgbọ́wá-Ìkòsì)..
wikipedia
yo
Àwọn olóyè kan náà wà tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Abọ́wá, ṣùgbọ́n ìpele-ìpele la tò wọ́n sí..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ ni Olóyè arọ, Olúwo, Ọ̀dọ̀fin àti Balógun.Lásìkò Ogun, Ìlú Àgbọ́wá-Ìkòsì ní Olú agbègbè ìjọba Ìkòsì, èyí tí wọ́n pè ní Ìkòsì District Council..
wikipedia
yo
Ibẹ̀ ni ibùdó ti àwọn èèyàn n farapamọ́ sí, pàápàá lati Imota, funfun, ọta àti òwú..
wikipedia
yo
Àgọ́-Ìmọ̀ta làwọn ará Ìmọ̀ta farapamọ́ sí ní tiwọn, àwọn ara funfun farapamọ́ sí Àgọ́-Yínfun, àwọn ti Ọ̀tà farapamọ́ sí Àgọ́-Ọ̀tà bẹ́ẹ̀ làwọn ara Òwu farapamọ́ sí Àgọ́-Òwu..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn ogúnléen yìí lo padà sí ìgbèríko wọn lẹ́yìn ogun..
wikipedia
yo
Àwọn obìnrin ajìjà-n-gbara tàbí àwọn obìnrin akọya ìlú Abeokuta ti ọdún 1940, jẹ́ ẹ̀gbẹ́ ìgbìmọ̀ tó múnádóko, tó sì ní jà fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Àwọn ẹgbẹ́ obìnrin Abeokuta fi ẹ̀hónú wọn hàn sí ètò ìṣèjọba amúnisìn àwọn Gẹ̀ẹ́sì, ẹgbẹ́ yí lòdì sí kí àwọn obìnrin má a san owó-orí ní ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
àwọn obìnrin ìlú Abeokuta yìí gbàgbọ́ pé lábẹ́ ìjọba amúnisìn, àwọn ètò ọrọ̀ ajé wọn kò tẹ̀síwájú, lákòókò tí owó-orí ti ìjọba ń gbà tún pọ̀ sí i..
wikipedia
yo
bákan náà, àwọn ẹgbẹ́ obìnrin yìí sọ wí pé kò yẹ rárá kí wọ́n má a san owó-orí lọ́tọ̀, ni wọn ìgbà tí àwọn ọkọ wọn ti ní san-án..
wikipedia
yo
Síwájú sí i, ó yẹ kí àwọn obìnrin náà lẹ́tọ̀ọ́ láti ṣe aṣojú ní ìṣèjọba agbègbè.Gẹ́gẹ́bí èròńgbà wọn, ìjọba gba àbádòfin kí wọ́n fún àwọn obìnrin láyè láti kópa..
wikipedia
yo
Wọ́n sì fún àwọn mẹ́rin láyè láti ṣe aṣojú ìjọba ní agbègbè..
wikipedia
yo
Òpin sí débá kí obìnrin má a san owó-orí ní ìlú Ẹ̀gbá àti ilẹ̀ Nàìjííríà..
wikipedia
yo
Ìlú Abẹ́òkúta jẹ́ ìlú tí àwọn ẹ̀yà Yorùbá ń gbé, tí ó sì wà ní gúúsù ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1830 ni wọ́n dá Ìlú Abẹ́òkúta sílẹ̀, tí àwọn Ẹ̀gbá àti Òwu jẹ́ olùgbé àkọ́kọ́ lórí ilẹ̀ náà.Ní ọdún 1850, tí ètò ìjọba amúnisìn ti ìlú Gẹ̀ẹ́sì bẹ̀rẹ̀ láti fa ìṣàkóso rẹ̀ sí Ìlú Abeokuta àti àwọn àdéhùn pẹ̀lú àwọn ọmọ bíbí Ẹ̀gbá.Ìwé Àdéhùn yìí ló fàyè gba àwọn gbogbo ìlú Ẹ̀gbá lápapọ̀ kí ìbáṣepọ̀ tó dán mọ́rán lè wà lórí ètò ọrọ̀ ajé wọn láti ìletò kan sí míràn àti ibodè ìkan dé mìíràn..
wikipedia
yo
Kí ààlà àti ètò ọrọ̀ ajé wọn pẹ̀lú ìlú Èkó fún ìgbaradì ètò òmìnira túnbọ́ rọrùn láti lée bọ́ lọ́wọ́ ìṣèjọba amúnisìn ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Àdéhùn yìí ti fún àwọn èèyàn Ègbá ní òmìnira tó ní orí ètòlọ́rọ̀ ètò-ọ̀rọ̀ tiwọn, ṣùgbọ́n ní ìkẹhìn, ìjọba Gẹ̀ẹ́sì wá ọ̀nà láti làjà ní ètò àdáṣe lẹ́hìn ìdààmú olóṣèlú kan ní ọdún 1897..
wikipedia
yo
Ìjọba Gẹ̀ẹ́sì béèrè àtúntò ètò òṣèlú ìlú náà, eléyìí ló ṣokùnfà dídá ijọba Egba United (EUG) sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣáájú sí ètò tuntun, àwọn ìgbìmọ̀ agbègbè ní àdéhùn pẹ̀lú pé ó kéré jù, obìnrin kan gbọ́dọ̀ wà lára àwọn aṣojú..
wikipedia
yo
EUG, lára àṣà wọn tẹ́lẹ̀rí, ọkùnrin nìkan ni wọ́n fi ń ṣe aṣojú kí iṣẹ́ ìdàgbàsókè àti ètò amáyédẹrùn bèrè ní ìlú Abeokuta..
wikipedia
yo
EUG ṣe àwọn iṣẹ́ àkànṣe àti ìdàgbàsókè ohun amáyédẹrùn, bí i ètò ọrọ-ajé, sísè àwọn ojú ọ̀nà, àti dókòwò pẹ̀lú ilẹ̀ òkèèrè, nípa ká fi àwọn nkani IIoko,o,o è-pupa, obì,àá àti aṣàkà.n..
wikipedia
yo
ii Ìparíọdúnn 1800s, Acòkúòkú tìdí ilú nla tó lókìkí tó sì gbajúmò lórí ètò ọrọ̀ ajé láàrín àwọn ìlú míràn íio àìjíríàaàati éewọ́n dádúró bí Ìlú tó ti gba Owitirẹ̀.Àwọn ìtọ́kasíìtàn ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Arewa jẹ́ ọ̀rọ̀ Hausa tí ó jẹ mọ́ ede Gẹẹsi "ariwa." Ó jẹ yọ lati ọ̀rọ̀ Hausa èyí tí ó túmọ̀ sí ariwa..
wikipedia
yo
Lápọ̀pọ̀, a ma fi n ṣe àdáyanrí ipò olóṣèlú, láti ìgbà tí ilẹ̀ kámá ṣòkòtò ti ṣubú..
wikipedia
yo
"KWA Arewa" tumo sí ilẹ̀ ariwa, Arewa naJéríyà si tumọ si Nothern Nigeria..
wikipedia
yo
A maa ń lọ wan ní ilẹ̀ Hausa lati ṣapejuwe itan ile naa, èyí ti o wa loke odo Niger.Lílo arẹwà ninu Oro....
wikipedia
yo
Ninu itan-akọọlẹ ti Nigeria ni pataki, a maa n lo lati tọka si pre-1967 Northern Region, Nigeria ..
wikipedia
yo
Púpọ̀ lára ilẹ̀ àríwá wà ní ìṣọ̀kan ìṣèlú ní ẹ̀yà náà, eléyí tí ó ní éeákósọnù oríṣióìjẹ́ràn ilé UU O lè fún ilée Haurokógún tilẹ̀ KáG Sokoto sorí ẹrú àti Ọ̀tọ̀ Caliphate Calite ni lábẹ́ ìjọ a íệệothern Nigeria Prov Bank lábẹ́ ìjọba Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Awon ara Ekun ariwa ni ile Nigeria, gegebiAlapejọ Arewa, Apejọ Arewa Media ti o wa ni Kaduna,eyi Ile jọmọ ati Ile Igbimọ Arewa ati Arewa People's congress jẹ apẹẹrẹ ti eyi..
wikipedia
yo
Àwọn ẹgbẹ́ wọ̀nyí kò ságbèrò òmìnira láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, wọ́n sì dojúkọ ìṣọ̀kan àṣà ti agbègbè Hausa – Fúlàní èyítí ó jẹ́ ọ̀pọ̀ jùlọ ní àríwá orílẹ̀-èdè náà..
wikipedia
yo
A ti fi ẹ̀sùn kan arẹwà pé ó faagun ìṣèlú ìjọba ati ti aṣa láti mú ìpínlẹ̀ àpapọ̀..
wikipedia
yo
Ìtàn ilẹ̀ Nìjẹ̀rjẹ́ografi ilẹ̀ Nàìjíríààìtan ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo