cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
ó ṣe agbéréjáde fún ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀ pẹ̀lú eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Therapist's Therapy.. | wikipedia | yo |
O tun ti fi owo fun aláboyún kan ni ile-iwosan 3-H Clinic and Maternity to wa ní ìlú Warri, Ìpínlẹ̀ Delta.Àkójọ Àwọn eré rẹ̀àwọn sinimá àgbéléwò rẹàwọn eré tẹlifíṣọ̀nù rẹàwọn ìyẹ́sí rẹàwọn Ìtọ́kasí àwọn ará Gogoogoawọn Ọjọ́ìbí ní 1992awon ènìyàn Alààyèawon osere ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Eyi ni atojo awon orile ede olominira ni agbaye pelu alaye lori ipo ati gbajumo won.. | wikipedia | yo |
Àpapọ̀ wọn jẹ́ Enìkanlénígba (206) tí a lè pín sí abala mẹ́ta tí ó dá lé ìbáṣepọ̀ wọn pẹ̀lú àjọ àgbáyé, United Nations, tí wọ́n jẹ́ 193, àti àwọn yòókù, méjì nínú wọn sì wà lábẹ́ ìwòye Observer States ti mọ́kànlá (11) Kòsí lára wọn.. | wikipedia | yo |
Abala ‘Ipò Òmìniralo ṣàfihàn àwọn Orílẹ̀-Èdè tí òmìnira wọn kò í ti í dúró ṣinṣin, wọ́n jẹ́ orílẹ̀ èdè 190, àti ipò àwọn mìíràn bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Ṣíṣe àtòjọ àwọn orílẹ̀ èdè báyìí máa ń ṣòro, nítorí kò sí mọ́mọ tàbí àmúyẹ kan pàtó láti dá orílẹ̀ èdè olómìnira mọ̀.. | wikipedia | yo |
Fún àlàyé sí i lórí àwọn àmúyẹ tí a wò láti ṣe àtòjọ àwọn orílẹ̀ èdè wọ̀nyí, ẹ jọ̀wọ́, ẹ wo abala ìsàlẹ̀ yìí criteria for lẹ́tọ̀ọ́síontẹ́.. | wikipedia | yo |
Àwọn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni a gbàgbọ́ pé wọ́n ní ipò dé facto gẹ́gẹ́ bi ilẹ̀ Olómìnira, bí ó ti wù kí ó rí, èyí kì í ṣe Ìfọwọ́sí pé wọ́n jẹ́ ilẹ̀ Olómìnira tí ó bá òfin mu.Àtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè Olómìnira Àgbáyéàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Monica Omorodion Swaida (tí ọjọ́ ìbí rẹ̀ jẹ́ 5 Oṣù Kaàrún) tí a mọ̀ sí Monicazation jẹ́ òṣèrébìnrin, akọrin, àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ Máàdámidódòfo kan.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n bí Swaida sí ṣùgbọ́n ó dàgbà ní ìlú Warri, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Nana Primary School ní ìlú Warri, àti ilé-ìwé girama Mount Wachusett Community College ní ìlú Massachusetts .ní àkókò tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga University of Massachusetts Lowell, Monica jẹ́ asíwájú àwọn ẹgbẹ́ oníjó ní ilé-ẹ̀kọ́ náà.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ère ijó, ó sì tún kọ ewì fún ẹgbẹ́ eré orí-ìtàgé nígbà náà.. | wikipedia | yo |
Ó maá n tẹ́tí sí orin Majek Fashek, ẹnití ó pè ní àwòkọ́ṣe rẹ̀.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀orin kíkọ Ororodion bẹ̀rẹ̀ sí ní kọrin láti ọmọ ọdún mẹ́rìnlá.. | wikipedia | yo |
Ó pàdé àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ òṣìṣẹ́ akọrin bíi Sam Morris àti Majek Fashek, ó sì maá n lọ sí ilé-ìṣeré fún ìdánilẹ́kọ̀ọ́.. | wikipedia | yo |
Ó máa ń tẹ̀lé Majek Fashek káàkiri lọ síbi àwọn iṣẹ́ orin rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Monicazation ṣe àgbéjáde àkójọ àwọn orin rẹ̀ tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Monicazation ní Oṣù Kẹẹ̀sán Ọdún 2014.Iṣẹ́ òṣèré Omorodion ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù gígùn tó fi mọ́ Affairs of the heart ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Joseph Benjamin àti Stella Damasus ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún kan náà, ó tún kópa nínu eré Burning Love, èyí tí óbẹ̀ Joe kọ ìtàn rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó tún ti gbé eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Faces of Love jáde, èyí tí ó padà gba àmì-ẹ̀yẹ.Àwọn orin tí ó ti kọàwọn àṣàyàn orin àdákọ rẹ̀ "Atgif" (2017) "Under Your influence" (2016) "Jesus" (2015) "Mambo" (2015) "moved on" (2015) "NA You" (2015) "Palava dey" (2015) "My Baby is Gone" (2015)Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè Ọdún ará ará ibi Ọjọ́ìbí Odi (Àwọn Ènìyàn Alààyè).. | wikipedia | yo |
Beverly Naya (tí àbísọ rẹ̀ jẹ́ Beverly jíkànkò Bassey; tí wọ́n bí ní 17 Oṣù Kẹẹ̀rin Ọdún 1989) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti òṣèré tí ó ní ìlérí jùlọ níbi ayẹyẹ Best of Nollywood Awards ti ọdún 2010.. | wikipedia | yo |
Ó tún gba àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó yára tayọ jùlọ níbi ayẹyẹ City People Entertainment Awards ti ọdún 2011.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ ìlú Lọ́ndọ̀nù ni wọ́n bí Beverly sí, ó sì jẹ́ ẹyinjú àwọn òbí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe iṣẹ́ òṣèré nígbà tí ó n kàwé lọ́wọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Brunel University ní ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún.. | wikipedia | yo |
O kẹkọọ kikọ itan-ere lati ile-ẹkọ giga Roehampton University.. | wikipedia | yo |
O tọka si Ramsey Nouah ati Genevieve Nnaji gẹ́gẹ́ bi àwọn àwòkọ́ṣe rẹ.Iṣẹ iṣe rẹ o bẹrẹ ere ṣiṣe ni ọmọ ọdun mẹ́tàdínlógún.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2011, wọ́n mu gẹ́gẹ́ bi òṣèrébìnrin tó yára tayọ jùlọ níbi ayẹyẹ City People Entertainment Awards.. | wikipedia | yo |
whereas coming to this industry, I can build a brand as well as shoot films more often and be given a more diverse amount of scripts.. | wikipedia | yo |
So, I decided to Come back for that reason"Àkójọ awon ere re guilty pleasures (2009) Death Waters (2012) Tinsel Home in exile Alan Poza forGetting June Make a Move Up Creek Without a Paddle Strict Weekend Getaway ...When Love Rest (2014) Brother's Keeper (2014) Before 30 (2015-) Oasis (2015) Skinny girl in Transit (2015) Suru l'ere (2016) The Wedding Party (2016) The Wedding Party 2 (2017) Chief Bookshop (2018) Dinner Affairs of the heart Juvarro Ju Arbitration tòótọ́ in sickness and Health ìyẹ́sí rẹàwọn Ìtọ́kasí awọn Ọjọ́ìbí ni 1988 ni Igbimọ Aeye Ara Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Abdullahi Dan kanajeji, tí a mọ̀ sí Abdullahi Burja, jẹ́ Ọba ìlú Kano kẹrìndínsun.. | wikipedia | yo |
Látàrí dídá ìbáṣepọ̀ àti Adéyín Okòwò tí ó péye sílẹ̀, butja ni ó yí ìlú Kano kúrò sí ìlú ìṣòwò tí a mọ Kano àti àwọn ará Kano sí lóde òní ó jẹ́ ọba Hausa àkọ́kọ́ tí ó tẹríba fún ìlú Bornu tí èyí sì jẹ́ kí àjọṣepọ̀ tí ó dánmọ́rán wà láàrín wọn tí èyí sì jẹ́ kí okòwò wọn gbòòrò láti gabe sí Bornu.. | wikipedia | yo |
O si tun jẹ ọba akọkọ ti o maa kọkọ ni ràkúnmí ni gbogbo ilẹ̀ Hausa.. | wikipedia | yo |
èyí sì fa kí ìṣòwò ẹrú gbòòrò láti Kano sí gúúsù sí Bornu.. | wikipedia | yo |
Abdullahi Burja nípasẹ̀ Galatẹ́nì rẹ̀ ṣẹ̀dá àwọn ìletò ẹrú tuntun mọ́kàǹgbá, tí ọ̀kọ̀ọ̀kan tó bí ẹgbẹ̀rún àwọn ẹrú tí ó ìpín dọ́gba láàrin àwọn ẹrú okùnrin àti obìnrin.. | wikipedia | yo |
díẹ̀ díẹ̀, ìṣọ̀wọ́ ní ìlú Kano yípadà sí àwọn ọwọ́ mìíràn.. | wikipedia | yo |
Folake Oritsebémi Onayemi (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrin Oṣù Kẹwàá odún 1964) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àti olùkọ́ ní University of Ìbàdàn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tó kàwé gboyè ọ̀mọ̀wé nínú ìmọ̀ FIṣẹ̀ríFI, PhD gbbala Classics.. | wikipedia | yo |
Ìmọ̀ Classics lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ náà òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tó kàwé gboyè ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ nílẹ̀ Adúláwọ̀ Áfíríkà.. | wikipedia | yo |
O je ojogbon ninu afiwe Litireso Greco-Roman ati Naijiria, paapaa ju lo, asa ati ise to je mo obinrin láwùjọ.Eko Folake OnaYemi kawe gboye digírì ninu imo Classics ni University of Ibadan lodun 1986, bẹẹ naa lo te siwaju si i ti o sin tun kawe gboye di keji, followed by an ma lodun 1990, MPana lodun lodun, ati PhD lodun lodun; oun ni obinrin akoko to kawe gboye omowe ninu imo FIBUFIFIFI, PhD Classics Classics ni Naijiria, pelu akanṣe iwe gboye ti o pe akole re ni Fear of Women's Beauty in Classical and African/Yoruba Literature.. | wikipedia | yo |
Ọ̀NÀYemi, Folake (2002) Women and the Irtioonal in Ancient Greek and Yoruba Mythology, Ibadan Journal of humanistic Studies Nos 11& 12 pp.. | wikipedia | yo |
YemiYemi, Folake (2002) courageous women in Greek and Nigerian Drama, antigone and tegonni, Ibadan journal of European Studies.. | wikipedia | yo |
Ogun Gurin ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ mọkandi, oṣù kẹrin, ọdún 1916 nígbà Kamẹrúùnù Campaign ni Ogun Àgbáyé àkọ́kọ́ ní Gurin, British Nigeria leti ààlà pẹ̀lú German Kamerun.. | wikipedia | yo |
Ogun náà jẹ́ ọ̀kan nínu àkọ́kọ́ tó tóbi jùlọ ti Jemani fi kọ́lu ìletò Britani.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ àṣeyọrí fún ìfèsì Britani sí ipa Jemani.Ìtàn ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Bauchi Emirate jẹ́ ẹ̀yà Fulani tíwọ́n sẹ̀sílẹ̀sílẹ̀Bauchi Emirate jẹ́ ẹ̀yà Fulani tíwọ́n gbẹ́ kalẹ̀ ní bíi ìgbà lọ́ odún sẹ́yìn ní ìpínlẹ̀ Bauchi loni, nílẹ̀ Nigeria, tí olú ìlú rẹ̀ jẹ́ Bauchi .. | wikipedia | yo |
Emirate yìí wà lábẹ́ ìdáàbòbò ìlú Gẹ̀ẹ́sì ni àkókò ìjọba amúnisìn.Ìtàn Bauchi Emirate.. | wikipedia | yo |
Kí Ogun Fulani tó bẹ̀rẹ̀ àwọn ẹ̀yà kékèké niwọ́n fi ìlù Bauchi Sebùgbé, lára wọn èdè Hausa ni wọ́n nsọ, tíwọ́n tíwọ́n ẹlẹ́sin mùsùlùmí.. | wikipedia | yo |
Ogun Fula èyítí Ykúbù Gerawa enití ó jẹ́ ọmọ ọ̀kan nínú adarí agbègbè ìlú ṣáájú rẹ̀ tí ó keko ní ìpínlẹ̀ Sokoto lábẹ́ Usman Dan Rye.Ni ó kógbà laarin ọdún 1809 sí 1818.Èyí lọmúkí wón wà lábẹ̀ àṣẹ àti ìdarí là títí di ọdún 1902.. | wikipedia | yo |
Nígbàtí ìjoba ilẹ̀ Britiko darí olú ìlú Bauchi laisi wàhálà kankan.. | wikipedia | yo |
Àwọn niwọ́n fagilé òwò ẹrú tóti gbilẹ̀ kíwọ́n tógbajoba… | wikipedia | yo |
Wọ́n sí fi Emir tuntun sísísí enitì ó kú lẹ́yìn oṣù pẹ́pẹ̀tẹ̀ tó ṣù.dún 1904 Emir mìíràn tó dìpọ̀ rẹ̀ ṣe lọsí lálọ tilẹ̀ ògé.[2] Ó gba gba àwọn olóṣẹ I Í gugu ní wọ́n ma ń jẹ́ lami ni tó ṣṣ ìpínlẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ogun Àdùbí (ti àwọn ÈÈYÀN tún mọ̀ sí rògbòdìyàn Ẹ̀gbá) jẹ́ rògbòdìyàn tó wáyé nínú Oṣù Kẹfà sí Oṣù Keje ọdún 1918 ní àwọn ìlú tí ìjọba ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì ń ṣàkóso ní ilẹ̀ Nàìjíríà, nítorí àfikún owó orí tó wáyé láti wáyé náà.. | wikipedia | yo |
Àwọn alákòóso ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì ló gbé ètò owó orí yìí kalẹ́ àti bí wọ́n ṣe ń fipá mú àwọn èèyàn ṣiṣẹ́ lásìkò náà.. | wikipedia | yo |
Lọ́jọ́ keje oṣù kẹfà, làwọn alákòóso ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì mú àwọn àáadọrin olóyè ilẹ̀ Ẹ̀gbá sátìmọ́lé, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì tún fi òfin lé e pé ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ fa wàhálà kan, àti pé kí àwọn tó n tako owó orí tuntun náà yọ̀nda ohun ìjà olóró tí wọ́n ń lò, kí wọ́n sanwó orí wọn, kí wọ́n má sì dìtẹ̀ aṣáájú.Ogun náà lọ́jọ́ kọkànlá, àwọn jagun-jagun, tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ dé láti ojú ogun ní apá ìlà-oòrùn ilẹ̀ Áfríkà, ni wọ́n pè, wá paná rògbòdìyàn ọ̀hún, kí alaafia lè jọba.. | wikipedia | yo |
Lọ́jọ́ kẹtàlá, oṣù kẹfà náà, àwọn ọlọ̀tẹ̀ ilẹ̀ Ẹ̀gbá fa àwọn irin tí wọ́n ṣe fún rélùwéè ní Agbẹ̀sí tu nílé, wọ́n sì já ọkọ̀ ojú irin tó wà lórí eré kúrò lójù ọ̀nà.. | wikipedia | yo |
Àwọn ọlọ̀tẹ̀ yóokù bá àwọn ibùdókọ̀ ọkọ̀ ojú irin tó wà ní Wasinmi jẹ́, wọ́n sì tún ṣekúpa aṣojú ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì; ọba Ọ̀ṣilẹ̀, tó jẹ́ adarí apá àríwá-ìlà-oòrùn nílẹ̀ Ẹ̀gbá, èèyàn dúdú ní Ọ̀ṣilẹ̀ yií.. | wikipedia | yo |
Fún ọ̀sẹ̀ mẹ́ta làwọn ọlọ̀tẹ̀ ilẹ̀ Ẹ̀gbá àti àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì fi kọjú ìjà sí ara wọn ní Otite, Tapọ̀po, Mokkikì àti Lala ṣùgbọ́n nígbà tó di ọjọ́ kẹwàá, oṣù keje, wọ́n ti paná ìdìtẹ̀ yìí, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì mú àwọn ọlọ̀tẹ̀ kan sí àtìmọ́lé bó tiẹ̀ jẹ́ pé wọ́n pa àwọn kan nínú wọn dànù.Ohun tó ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ogun àwọn èèyàn tó tó ẹgbẹ̀ta làwọn ọmọ ogun ṣẹ́kùpá, nínú wọn náà ní aṣojú ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Ọba Ọ̀ṣilẹ̀, bó tiẹ̀ jẹ́ pé ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ọ̀rọ̀ ilẹ̀ tó fàjà lásìkò náà ṣùgbọ́n tí kò jẹ mọ́ ọ̀rọ̀ owó orí tún pẹ̀lú ohun tó fà á tí ọ̀pọ̀ èèyàn fi pàdánù ẹ̀mí wọn.. | wikipedia | yo |
Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló mú kí wọ́n fagilé òmìnira ilẹ̀ Ẹ̀gbá lọ́dún 1918, tí wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ ìfipámúnisìn láwọn agbègbè náà; bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì tún sọ gbígba owó orí di ọdún 1925.. | wikipedia | yo |
Àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì tí wọ́n paná ọ̀tẹ̀ yìí ni wọ́n tún fi àmì-ẹ̀yẹ Africa General Service Medal dá lọ́lá.Ìtàn ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Idris Alooma, Idris Ibn ‘Ali (Alooma), eni ti a tun le pe ni ''Idriss Alooma o tun jẹ ''Mai’’ Ọba awon kanem-Bornu Empire, ti a le ri ni agbebgé Chad, Kamẹrúùnù, Nìjẹ̀r, Nìjẹ̀r ati Naijiria(Orílẹ̀-èdè Olómìnira 🙂 | wikipedia | yo |
Bí àgbékalẹ̀ ọ̀rọ̀- orúkọ rẹ̀ ṣe rí ni yín ''Idris Alawmá’’ tàbí ''Alauma’’ | wikipedia | yo |
1990.Àwọn ọba ati ìjòyè ní Naijiriàìtan ilẹ̀ Naijiriàìtan ilé Chad.. | wikipedia | yo |
Ebube Nwagbo jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O tun je oludakoogbọ̀nà.Ise re Nwagbo wá lati Uschu, ní ìjọba agbègbè Aguata Local Government Area, Ìpínlẹ̀ Anámbra, ṣùgbọ́n ó dàgbà ní ìlú Warri, Ìpínlẹ̀ Delta.. | wikipedia | yo |
Ó kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ Ìgbéròyìn síta ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Nnamdi Azikiwe.Àtòjọ àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe rẹ̀ ní ọdún 2003 nígbà tó wà lọ́mọ ogún ọdún. | wikipedia | yo |
Arki by Love Eyes of the Nun before my Eyes against my Blood Royal Palace Mama, I Will Die For You Power of Trust Not Yours! ojuju Calabar Me Without You (2019)Àwọn Ìtọ́kasí Àwọn Eniyan Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1983àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Queen Nwokoye (tí a bí ní 11 Oṣù Kẹẹ̀jọ, Ọdún 1982) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
ó gbajúmọ̀ fún kíkó ipa olú-ẹ̀dá-ìtàn nínu eré kan ti ọdún 2014 tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Chetanná, èyítí ó sọkùn fà tí wọ́n fi yàán fún àmì-ẹ̀yẹ "Òṣèré tó dára jùlọ" nibi ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards .Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ Ìpínlẹ̀ Èkó ni wọ́n bí Nwokoye sí, ṣùgbọ́n àwọn òbí rẹ̀ wá láti Ìpínlẹ̀ Anámbra.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Air Force Primary School.. | wikipedia | yo |
O si tun pari ẹkọ girama rẹ ni Queen's College ti Ilu Enugu ṣaaju ki o to lọ si Ile-ẹkọ giga Yunifasiti Nnamdi Azikiwe ni Ilu Awka, Ipinle Anambra nibi ti o ti kẹkọọ Imọ Awujọ.. | wikipedia | yo |
Ó dàgbà pẹ̀lú ìpinnu láti di amòfin.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ láti ìgbà tí ó ti ṣe àkọ́kọ́ eré rẹ̀ ní ọdún 2004, Nwokoye ti ṣe bẹ́ẹ̀ kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù ti Nàìjíríà, tó sì tún gba àwọn àmì-ẹ̀yẹ lóríàtòjọ àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ ní Men (2004) lárù (2004)The Girl Is Mine (2004) Risk (2004)Save The Baby (2005) Eroko (2005) The Word (2006) To Girl (2006)Last (2006) Kọ́lle (2006) Of Faith (2006) Dance (2006) of Interest (2006)The Last Vper (2007) You Are M (2007) (2007) (2007) Me Heaven (2007) Of Time (2007) In (2007) In Shost (2007) Civilian (2007) Cargos (2007) Ever Besting (2007) Romance (2007) The Evil Queen (2008) of Justice (2008) Oja (2008) of a Slave (2008) Eẹbọ (2008) London (2008) of the Niger (2009)Personal (Personal) (2009) of Gentle (Men (2009) Mo of the League (2009) Friend (2009) of Justice (2010)Mirror of Life (2011) of Mirror of Life (2011) (2011) Diskwo (2014) (2012) (2013) Mbano (2014) (2016) (2016:New House (2017) Barona Bars (2015) Cofper buburu (2016 tí a yàn àwọn ìyẹ́sí rẹ̀ ayé rẹ̀ Nwokoye ti ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú Ọ̀gbẹ́ni Uzoma, ó sì ti bí àwọn ọmọ ìbe okùnrin àti ọmọbìnrin kan.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ita dédé àwọn ènìyàn Ìáá ní 1982 ní 1982 ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí Ngozi Nwosu ní Ọjọ́ Kínní, Oṣù Kẹẹ̀jọ Ọdún 1963.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ gbajúgbajà òṣèrébìnrin àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe rẹ̀ pẹ̀lú ṣíṣe eré èdè Yorùbá ṣááju kí ó tó wá kópa nínu eré èdè ígbò kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Living in Bondage.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ Nwosu jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Arochukwu ní Ìpínlẹ̀ Ábíá.. | wikipedia | yo |
Ó ní ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní St Paul Anglican School, Idi Oro.. | wikipedia | yo |
Lẹhin naa, o lọ si Maryland Comprehensive High School ni Ilu Ikeja, Ipinle Eko.. | wikipedia | yo |
O gba awọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fun iṣẹ́ oṣere rẹ labẹ Reverend Fabian ọkọ ni ile-iṣere Royal Theatre Art Club School.O ṣaisan ni ọdun 2012, ṣugbọn o gba itọju ni ile okere nipasẹ iranlọwọ ijọba ati awọn ile-iṣẹ miran.iṣẹ iṣe rẹ o bẹrẹ iṣẹ oṣere rẹ ni akoko igba ti o wa ni ile-iwe.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa gẹ̀gẹ̀ bi “Madam V Boot" nínú eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Ripples.. | wikipedia | yo |
Ó tún ti kópa gẹ́gẹ́ bi "Peace" nínu eré tẹlifíṣọ̀nù aláwàdà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Fuji House of Commotion (èyí tíAmaka Igwe gbé kalẹ̀).. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2018, ó kópa gẹ́gẹ́ bi “Ene nínu fíìmù “Sade.. | wikipedia | yo |
Ó tún tí ṣe olóòtú àwọn eré bíi Evil Passion, Stainless àti ètò rédíò kan tí n ṣe Onga.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1963àwọn ènìyàn Alààyèàwọn òṣèré ará Nàìjíríà.Òhun ọmọ Igbo.. | wikipedia | yo |
Emma Chukwugoziam Obi (tí a bí ní 18 Oṣù Keèje, Ọdún 1988) tí a mọ̀ sí Emma Nyra jẹ́ òṣèrébìnrin, akọrin, àti afẹwàṣiṣẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ Emma Nyra ni a bí tó sì dàgbà ní agbègbè Tyler ní ìlú Texas, orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ó ní ètò-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní ìlú yìí bákan náà, níbẹ̀ ló sì tún ti gba oyè-ẹ̀kọ́ nígbà tí ó fi lọ sí Texas Southern University tó sì kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ ìṣàkóso ìlera.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, ó gbéra wá sí Nàìjíríà láti lépa iṣẹ́ orin àti afẹwàṣiṣẹ́.Iṣẹ́ iṣẹ́ iṣẹ́iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀ Emma Nyra ṣe àgbéjáde àwọn àkọ́kọ́ orin rẹ̀ tí àkọ́lé wọn ń ṣe "Do It" àti "Everything I Do" ní ọdún 2011 ní àkókò tí ó wà ní Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Lehin ti o pada si Naijiria ni odun 2012, o bere si ni sise pelu D'tun ati Ayaya, awon ti o ti pade ni odun 2010 ni Amerika.Ni odun 2013, Emma Nyra gba ami-eye osere ti o ni ileri julo nibi ayeye Nigeria Entertainment Awards.. | wikipedia | yo |
O ti wa sise pelu awon osere akorin bii Davido, Patoranking, Olu Maintain ati awon miran.. | wikipedia | yo |
Àkọ́kọ́ àkójọpọ̀ àwọn orin rẹ̀ tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Emma Nyra Hot Like Fiya Vol.. | wikipedia | yo |
1 Kò tíì jẹ́ Gbígbéjáde.Iṣẹ́ fíìmù rẹ̀ yàtọ̀ sí orin kíkọ, Emma Nyra tún jẹ́ òṣèré.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu àwọn fíìmù mẹ́ta tí àkọ́lé wọn ń jẹ́ American Driver, undebo àti The Re-Union.Àwọn ìyẹ́sí rẹàwọn Ìtọ́kasíàwọn Ìtàkùn ìjáde àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1988àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
UZZ Usman Adeyemi tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá Oṣù kọkànlá ọdún 1986, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá, olùgbéré-jáde, adarí eré, òun ni ó gbé eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ ọ̀gá Abuja jáde.Ó jẹ́ òṣèré tí ó ní agbáEA láti máa kópa nínu agbo Nollywood àti Kanywood lápapọ̀ là fara gbọ̀n ibìkan.. | wikipedia | yo |
Akitiyan yí sí ti fún ní ànfàní láti gba àwọn àmì-ẹ̀yẹ Ìfòpinrisi bíi àmì-ẹ̀yẹ Young Entrepreneur of the Year níọdún 2016 níbi ayẹyẹ “National Heritage Award”.Ìgbà Ewe ReUsman ni o jẹ́ ọmọ bibi Ipinle Kwara, amo wọ́n tó dàgbà ní ìpínlẹ̀ Kaduna, ó ti kàwé gboyè nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ nípa ìṣèlú àti ìmọ̀ nípa èdè Gẹ̀ẹ́sì ni ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì Abuja àti Yunifásítì Jóṣ ṣáájú kí ó tó lọ sí orílẹ̀-èdè South Africa láti tún lọ kọ́ ìmọ̀ síwájú sí.Iṣẹ́ rẹ̀ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí irú-lóge ní ọdún 2003, tí ó sì tún bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe ní àárín ọdún _*2013.. | wikipedia | yo |
Ó ti gbé àwọn eré ọlọkàn-o-jọ̀kan eré tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ jáde ní abẹ́ ilé-iṣẹ́ kannywood àti Nollywood pẹ̀lú+including ọ̀gá Abuja, which won Best Hausa Movie of the Year at the 2013 City People Entertainment Awards; ọ̀kan lára àwọn eré rẹ̀ tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ sinimá àgbéléwò tí ó dára jùlọ ní agbo kannywood ní ọdún 2014 níbi ayẹyẹ "City People Entertainment Awards", tí wọ́n sì tún yàn fún àmì-ẹ̀yẹ "eré tí àwòrán rẹ̀ dára jùlọ" níbi ayẹyẹ 2014 Nigeria Entertainment Awards ní Maja.Àwọn ami-eye rẹàwọn aṣayan ere rèé tún le wo list of Nigerian Film producers Ìtọ́kasí ní Ọjọ́ìbí ní 1986Nigerian Film Anace Directors Film Ìbéèrè yangàn From From Chets From Kwara of JosUniversity of Jos of Abuja Ibidọ́gba Gbogbo Ènìyàn Alààyè | wikipedia | yo |
Susan Luchi Watson tí ó jẹ́ òsèré Amẹ́ríkà àti ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá Oṣù kọkànlá ọdún 1981.. | wikipedia | yo |
Ó di lààmì-laaka látàrí ipa rẹ̀ tí ó ma n kò ní orí àwọn eré orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán Louie àti ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bi ẹ̀dà-ìtàn Beth Pearson nínú eré This is Us.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ Critics’ Choice Television Award for Best Supporting Actress in a Drama series .Igba ewe kò bí Waston ní ìlú Brooklyn ní ọjọ́ kọkànlá Oṣù kọkànlá ọdún 1981.Nígbà tí wọ́n bí àwọn òbí rẹ̀ méjèjì náà sí orílẹ̀-èdè Jàmáíkà.. | wikipedia | yo |
Oruko re "kẹlẹchi" ti Watson's n je ṣàfihàn re gege bi omo bibi eya Igbo ni orile-ede Naijiria, ti o tumo si OLÚWA ṣeun | wikipedia | yo |
Watson Obtained a Bachelor of Fine Arts degree from Howard University and a master of Fine Arts degree from the tiSch School of the Arts graduate acting program.Iṣẹ rewatson ti n kopa ni ori ere àtìgbàdégbà Louie lati ọdun 2012 titi di ọdun 2014.. | wikipedia | yo |
Ó tún ń kópa ninu NCTA, the following, ati the Blacklist.. | wikipedia | yo |
Ó tún kópa nínu eré oníṣe ti American Airlines Theatre ní ìlú New York, eré tí ọ̀gbẹ́ni Richard Greenberg kọ tí ó pe àrírí rẹ̀ ní a Naked Girl on the Appian Way ní ọdún 2005.. | wikipedia | yo |
Ó ti ń kópa lórí eré oníṣe onípele àtìgbàdégbà tí This is us náà gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn Beth pearson.waston tún pẹ̀lú Tom Hanks kópa nínú eré tí Fred Rogers gbé jáde tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ A Beautiful Day in the neighborhood ní ọdún 2019.Àwọn Àṣàyàn eré rẹàwọn Ìtọ́kasíìtàkùn ìjásóde American Television Actresse ènìyàn alààyèAfrican-American Actres Meter People of Jamaican descentàwọn Ọjọ́ìbí ní 198121-Century American Actres Stage Actres film Actresct from New York City From from Brooklyn.. | wikipedia | yo |
Bob-Manuel Obidimma Udokwu tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù Kẹrin, jẹ́ òṣèré, adarí eré, olùgbéréjáde àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríàoun ni ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Lifetime Achievement ní ọdún 2014 níbi ayẹyẹ 10th Africa Movie Academy Awards.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ ti òṣèrékùnrin amugbalegbe tí ó peregedé jùlọ ní bi ayẹyẹ àmì-ẹ̀yẹ ti 2013 Nollywood Movies Awards fún ipa ribi ribi tí ó kó nínú eré Adesùfẹ́.Ìgbé ayé rẹ̀ wọ́n bí ObidiMA ní ìlú Nkwe-ògidì, ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ariwa "Iimiimimili" ní Ìpínlẹ̀ Anámbra, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ ẹ̀yà igbó pẹ̀lú.ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti St.. | wikipedia | yo |