cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní ọdún 2019, ó kópa nínu eré Oriwe tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Haitata.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Franca Obiàánùju Brown (bíi ní ọjọ́ kẹtàdínlógún Oṣù Karun-ún, Ọdún 1967), jẹ́ òsèré lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O gba ami eye City People Movie Special Recognition Award lati odo City People Entertainment Awards ni ọdun 2016.Ibẹrẹ pẹpẹ aye ati ẹkọ rẹ Brown bẹrẹ ẹkọ ibẹrẹ pẹpẹ rẹ ni Ile Eko St Mary's Primary School ni Ilu Onitsha ni Ipinle Anambra..
wikipedia
yo
O gboye ninu imo ofin lati ile eko giga ti Ahmadu Bello University..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Jos níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ eré orí ìtàgé.Iṣẹ́ Brown gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré fún ipa tí ó kó nínú eré Behind the clouds..
wikipedia
yo
Kí ó tó kópa nínu eré náà, ó ma ń ṣe eré orí ìtàgé rán pé..
wikipedia
yo
Ó kópa nínu eré rán pé tí àrírí rẹ̀ jẹ́ Swam Karagbe..
wikipedia
yo
Brown jẹ́ adarí fún eré, òun sì ni ó darí eré Women at large.Ní ọdún 2019, ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ dáná sun ilé rẹ̀àmì ẹ̀yẹ ní ọdún 2016, ó gba àmì ẹ̀yẹ City People Movie Special Recognition Award lati ọ̀dọ̀ City People Entertainment Awards.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Cheche Bilongo (tí a bí ní 26 Oṣù Kínní, Ọdún 1974) jẹ́ òṣèrébìnrin, ònkọ̀tàn, àti olóòtú ọmọ orílẹ̀-èdè Kamẹrúùnù.Itọ̀ rẹ̀ Bilongo wá láti agbègbè-ààrin ti orílẹ̀-èdè Kamẹrúùnù..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ìwé Johnson College ní ìlú Yaoundé níbi tí ó ti ṣe àwọn ère ijó..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1987, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní lọ sí àwọn àtúnyẹ̀wò ẹgbẹ́ ìṣeré orí ìtàgé ti André Bang tí wọ́n pe orúkọ wọn ní Les paGayeurs..
wikipedia
yo
Níbẹ̀ ló ti há àwọn ọ̀rọ̀ tó wà fún akópa olú-ẹ̀dá-ìtàn sórí..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kan tí wọ́n àtirírí akópa olú-ẹ̀dá-ìtàn náà, Bilongo rọ́pò rẹ̀ láti kó ipa náà, èyí tí ó fún ní ànfàní láti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ ẹgbẹ́ náà.Bilongo kó ipa sinimá sinimá rẹ̀ nínu fíìmù tí Lga, L'Hétage ní ọdún 2000..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2005, Bilongo kópa gẹ́gẹ́ bi Sabine nínu eré tẹlifíṣọ̀nù N'taPhil..
wikipedia
yo
Bákan náà ní ọdún 2007, ó kópa gẹ́gẹ́ bí Pam nínu eré Hélène Patricia Ehuh kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Les Blessures Ingublesbles..
wikipedia
yo
ó di olóòtú fún ìkànnì Telifísọ̀nù CRTv ní ọdún 2009.Ní ọdún 2019, Bilongo ṣe àgbéjáde àkọ́kọ́ orin àdákọ rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ n jẹ́ "Le Temps dé Diparkún..
wikipedia
yo
Ó kọ orin náà ní èdè Beti fún ìyá rẹ̀ tí ó ti di olóògbé..
wikipedia
yo
Nadine Ibrahim (tí a bí ní ọdún 1993/1994 ) jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Itọ̀ rẹ̀ a bí Ibrahim ní ìlú Kàdúná ó sì dàgbà sí inú ẹ̀sìn Mùsùlùmí..
wikipedia
yo
Mohammed ti fìgbà kan jẹ́ òjíṣẹ́ ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ríi fún ètò àyíká..
wikipedia
yo
Láti ìgbà tí ó ti wà lọ́mọdé ni ó ti ní ìfẹ́ sí ṣíṣe fíìmù..
wikipedia
yo
Ó kó lọ sí Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rìnlá níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ṣíṣe fíìmù láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Gloucestershire University..
wikipedia
yo
ó tún máa ń ṣiṣẹ́ lórí àwọn iṣẹ́ àkànṣe fún Àjọ Àgbáyé pẹ̀lú ṣíṣe àwọn fíìmú tó dá lórí ìrírí ayé..
wikipedia
yo
Ibrahim jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n gbẹ́ ère tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Hakkunde jáde..
wikipedia
yo
Eré náà dá lóri ará Gúúsù Nàìjíríà kan tí ó ṣe alábàápàdé àṣà Ariwa fún ìgbà àkọ́kọ́.Ibrahim tọ́ka sí Tyler Perry, Alfred Hitchcock, Spike Lee àti Ang Lee gẹ́gẹ́bi àwọn àwòkọ́ṣe rẹ̀.Ó tún tọ́ka sí ìyá rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó tún ní ipa pàtàkì lóri rẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n dárúkọ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn ọ̀dọ́ olùbẹ̀rẹ̀jáde tí ó ní ìlérí jùlọ ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Nṣèṣedy ConTeh George (tí a bí ní ọdún 1979) jẹ́ olùdarí eré àti olóòtú ọmọ orílẹ̀-èdè Sierra Leone àti Kánádàìse rẹ̀ ìlú Freetown ni wọ́n bí George sí, ṣùgbọ́n ó lọ sí ìlú Kánádà ní àsìkò ìgbà èwe rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó lọ sí yunifásítì ìlú New Orleans pẹ̀lú owó-ìrànlọ́wọ́ ìwé kíkà..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn ìparí ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó gbajúmọ̀ iṣẹ́ fíìmù ṣíṣe tó sì n sọ àwọn ìtàn nípa fífọ́nká àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfríkà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2004, ó ṣe adarí fíìmù fún ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀ nígbà tí ó fi darí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Soldiers for the Streets, èyí tí n ṣàlàyé nípa akitiyan Ras King láti kọ́ àwọn ọ̀dọ́ lẹ́kọ̀ọ́..
wikipedia
yo
O se adari ere oniiriri ti akọle rẹ je Literature alive ni odun 2005..
wikipedia
yo
Yàtọ̀ sí ṣíṣe adarí eré, George tún ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi olóòtú fún àwọn eré bíi I Want to Be a Desi (apa kejì), Something Beautiful, Arts & Minds, Food & Drink TV àti The Marilyn Denis Show fún ìkànnì CTv..
wikipedia
yo
Láti ilé-iṣẹ́ rẹ̀ tí ó pè ní Mattru Media, ó ṣe àgbékalẹ̀ ètò tẹlifíṣọ̀nù kan tí a pè ní The Rhyming Chef BarBuda.ní ọdún 2008, ó darí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Circle of slavery pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn ọ̀rẹ́ àti àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ ní Sierra Leone..
wikipedia
yo
Eré náà dá lóri àwọn ìbátan ÀTIJỌ́ tí ó wà láàrin orílẹ̀-èdè Sierra Leone àti Kánádà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, George darí eré The Flying Stars pẹ̀lú owó tí Sundance documentary Film Fund gbé kalẹ̀..
wikipedia
yo
Eré náà gba àmì-ẹ̀yẹ eré ìrírí tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ Bronzelens Film Festival ti ọdún 2015.Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ Solnìkan for the Streets (2004) Literature Alive (2005) The Circle of slavery (2008) The Rhyming Chef BarBuda (2009) The Flying Stars (2014) Dudley speaks for Me (2016) Mr..
wikipedia
yo
Jane and Finch (2019)Àwọn Ìtọ́kasíàwọn Ìtàkùn ìjásóde Ngaddy ConTeh at the Internet Movie Databaseàwọn ẹ̀nìyàn alààyẹ̀..
wikipedia
yo
Jill Levenberg (tí a bí ní 20 Oṣù Kẹẹ̀sán, Ọdún 1977) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Gúúsù Áfríkà.Isẹ̀mí rẹ̀ Levenberg gbé ní agbègbè Kensington, ìlú Cape Town..
wikipedia
yo
Láti ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́fà ló ti ṣe àkọ́kọ́ eré rẹ̀ lórí ìpele nígbà kan tí ó fi kọrin ní ilé-ìṣeré Kensington Civic Centre..
wikipedia
yo
Ó kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré, bẹ́ẹ̀ ló sì tún jẹ́ alãpọn nínú ẹgbẹ́ akọrin ní àkókò ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
Levenberg lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga University of Cape Town níbi tí ó ti gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ eré ìtàgé àti èdè Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Levenberg kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré bíi Medea, Blood Brothers àti Orpheus in Africa ní ìbẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré tí ó tayọ jùlọ fún ipa rẹ̀ nínu Orpheus in AFRIssss kópa gẹ́gẹ́ bi Beulah nínu fíìmù ti ọdún 2015 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Abraham..
wikipedia
yo
Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2015, ó ti kópa gẹ́gẹ́ bi Mymòẹ̀nà Samsodien nínu eré tẹlifíṣọ̀nù alátìgbà-dègbà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Suidooster..
wikipedia
yo
Levenberg tún maá n ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ọ̀fẹ́ nípa eré yoga àti eré orí-ìtàgé fún àwọn ọ̀dọ́ ní ìlú Cape Town..
wikipedia
yo
Tina Mba jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n yàn fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tí ó tayọ níbi ayẹyẹ ẹlẹ́keè tí Africa Movie Academy Awardṣiṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2017, Tina kópa nínu àwọn eré bíi Isoken, Bariga Suger, Okafor's Law àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ, tí ìwé ìròyìn Pulse sì ṣe àpèjúwe rẹ̀ bíi “òṣèrébìnrin tí ó dára jù lọ́dún”
wikipedia
yo
Níbi ayẹyẹ Africa Magic Viewers Choice Awards ti ọdún 2017, wọ́n yàán fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tí ó tayọ jùlọ nínú eré aláwàdà..
wikipedia
yo
O ṣalaye wipe oun ko ba ti feran ere ori ipele ju sinima agbelewo lo tọba se wipe owo re po daada..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, ó kópa nínu eré afìfẹ́hàn kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Ufuoma, èyítí Ikechukwu Onyeka darí..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kẹẹ̀wá ọdún 2017, ó tún kópa nínu eré Ọmọye, èyítí ó jẹ́ láti lòdì sí ìfipábá́nbá́nnù
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017 kan náà ló kópa nínu eré Isoken ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Fúnkẹ́ Akíndélé àti Dakore Akande..
wikipedia
yo
O ko ipa iya kan to n fe ki omo re obinrin se igbeyawo ni kiakia.aṣayan awon ere re isoken Okafor's Law make a Move Married but living single Heroes and Zeroes Tango with Me the ganp Beneath Her Veil (2015) Three wise Men (2016) Banana Island Ghost (2017) The Bridge (2017 film) Nigerian Prince (2018) The Set Up (2019)ọ̀rọ̀ rẹ̀ ó jẹ́ ọmọ bíbí bí Ìpínlẹ̀ Enugu, ó si ti bi omo meji.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyèọdún Ọjọ́ìbí Kòsí (àwọn ènìyàn Alààyè)àwọn ọmọ Igbóàwọn ọ̀d ara Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Gloria Young (bi ni ojo kerin osu keji odun 1967) je osere ni orile ede Naijiria ti o gba ami eye Movie couple of the year lati odo City People Entertainment Awards ni odun 2018.ibẹrẹ aye ati eko rẹ won bi Gloria si Ipinle Abia..
wikipedia
yo
O lọ si Ile Eko Methodist Girls High School ní Yaba ní ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.IṢẸ́ GLORIA bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi oníròyìn..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bi òṣèré ní ọdún 2014 lẹ́hìn tí ó kó ipa Doris nínu eré Glamour girls.Ami ẹ̀yẹayé tí rẹ̀ Young ti ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú ẹlẹ́gbẹ́ Nollywood rẹ̀ Norbert Young àti pé àwọn méjéèjì ní ọmọ mẹ́ta papọ̀..
wikipedia
yo
Ìdíje eré bọ́ọ̀lù Tuntun kan ni wọ́n ṣètò ní pápá ìṣeré ti orílẹ̀-èdè ní Surulere, Ìpínlẹ̀ Èkó ní òmíràn láti ṣe ayẹyẹ ‘jù' Fadaka rẹ̀ ní Nollywood.Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣe ṣe Fleecity passionate Appeal the Soul that Sinneth wanted at all cost back to life the return deadly affair Glamour girlsiìtàn aye rẹ̀ Gloria jẹ́ ìyàwó fún Nobert Young, wọ́n sì ti bí ọmọ mẹ́ta.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Princess OsayoMwanBor Peters jẹ́ akọrin ìhìnrere àti òṣèré ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Peters sí ìlú Benin ní Ìpínlẹ̀ Ẹdó..
wikipedia
yo
Ó gba nce rẹ̀ nínú ìmọ̀ biology àti Integrated Science láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti College of Education ní Benin ní ọdún 2006..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀ siwaju sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Benson Idahosa University lati gboye ninu imọ Mass Communication.Iṣẹ Peters bẹrẹ orin kikọ nigba ti o wa ni ọmọde..
wikipedia
yo
O wa ni ẹgbẹ akọrin ti awọn ọmọde ni ile ijosin ti awọn obi rẹ..
wikipedia
yo
O ti gbe orisirisi awon orin jade bii KPomwen ṣuṣu,huese, ose, ati ọ̀gbọ̀viọ̀sà..
wikipedia
yo
Oun ni oludasile ẹgbẹ lifted hands Initiative ati Princess Peters Foundation eyi ti o gbe kale lati le maa fi se iranlọwọ fun awọn alaini.Aṣa awọn ere ti o ti se what's within (2014) Destiny Gate home in exile girls are not S– (2017) about tomorrow Adesùsù ATM desperate love Singles clini eyeàwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Gnny Uzoma jẹ oṣere ni orilẹ ede Naijiria.ibẹrẹ pẹpẹ aye ati Eko rẹ wọn bi Gnny si Ipinle Enugu, ibè si ni o dagba si..
wikipedia
yo
Ó gboyè jáde nínú ìmọ̀ òṣèlú láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Ẹnú State University of Science and Technology.Iṣẹ́ Uzoma bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe eré nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méjìdínlógún..
wikipedia
yo
Ó gba àmì ẹ̀yẹ Revelation of the Year láti ọ̀dọ Best of Nollywood Awards ní ọdún 2015..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ Most Promising Actress láti ọ̀dọ City People Movie Award.Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣe I wish she would the shopgirl birthday bash Husband of Lagos the vendor our Society Best of the Game Classical Fraud Royal DAD Eagles Joseph Who Killed Chief A Love Story Emem and Angie Reconciliation the Gateman Baby Shower baby Mama commitment Shy SRERE A Face in the as caught in Between King of Kings Love in the Wrong Places the wasHerman once upon an Ruse Bond (2019)Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Obianuju Blessing Okeke ti o gbajumọ gẹgẹ bii mẹwa Okeke jẹ oṣere ni orilẹ edè Naijiria ti o gbajumọ fun ipa ti o ko ninu ere Mission to Nowhere ati the Barrister..
wikipedia
yo
Ó gboyè nínú ìmọ̀ eré orí ìtàgé láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Yunifásítì Nnamdi Azikiwe..
wikipedia
yo
Ni odun 2012, o fe ilakh, won si se igbeyawo won ni ile ijosin ti Saint Barth Anglican Church ni Ipinle Eko.Iṣẹ ni odun 2006, Okeke ko ipa ọmọ ọdọ ninu ere Mission to Nowhere eyi ti tàbi Benson gbe kale..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017, ó gba àmì ẹ̀yẹ Next Up Artist láti ọ̀dọ Africa Movie Academy Awards fún ipa tí ó kó nínú eré náà.Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣeàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Linda Oosi (Bii ni ojo ketadinlogbon osu keje odun 1991)je osere ati atọ́kùn eto lori telefisonu ni orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
O gbe ipo keji ninu idije Miss Nigeria Entertainment ni ọdun 2011, o si gbe ipo kẹta nibi idije Miss Africanàdá ni ọdun 2011..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ láti ọ̀dọ ELOY Awards fún ipa tí ó kó nínu eré Desperate Housewives Africa..
wikipedia
yo
Oun ni oludasile LaofFoundation.ibẹrẹ pẹpẹ aye rẹ wọn bi Linda si Ilu Benin ni Ipinle Edo..
wikipedia
yo
Ó gboyè nínú ìmọ̀ Psychology láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti York University ní ọdún 2013.IṢẸ́ ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 2012, pẹ̀lú eré Family Secrets, In New Jersey èyí tí Ikechukwu ṣe adarí fún..
wikipedia
yo
Leyin ti o pada si iluNaijiria ni odun 2013, o farahan ninu ere King Akubu.
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017, ó kó ipa Adesùsù Demi nínu eré Fifty àti ipa Nor' nínú eré Jemeji..
wikipedia
yo
Oun ati ṣẹgun Arinze ni atọkun fun eto give n take National Jackpot..
wikipedia
yo
Ni osu kefa odun 2018, o wa laarin awon ti o se ipolowo fun campari Make it Red.Ami Ẹyẹawon itọkasi..
wikipedia
yo
Ufuoma Stacey McDermott (tí a bí ní 23 Oṣù Kẹẹ̀rin, Ọdún 1981) jẹ́ òṣèrébìnrin, afẹwàṣiṣẹ́, àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ a bí Ejenobor ní ìlú Benin ṣùgbọ́n àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ẹ̀yà Urhobo tí ó wá láti Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún méje, bàbá rẹ̀ fún ní orúkọ ìnagi tí n ṣe Isiọ (èyítí ó túmọ̀ sí “oníràwọ̀” ní èdè Urhobo )..
wikipedia
yo
Wọ́n sọ orúkọ rẹ̀ láti fi jọ ti gbájúmọ́ òṣèrébìnrin kan tí ó máa n ṣe atọ́kùn ètò The Pot of Life lóri ìkànnì NTA Benin.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ Ejenobor di aládélórí ní 23 Oṣù Kẹẹ̀rin Ọdún 2010 pẹ̀lú fífẹ́ Steven McDermott, ṣùgbọ́n ó yí orúkọ rẹ̀ padà sí Ufuoma McDermott ní 23 Oṣù Kaàrún Ọdún 2014 ní ilé-ẹjọ́ gíga ti ìlú Èkó.ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ó lọ sí Alama Private School ní ìlú Jos, Ìpínlẹ̀ Plateau..
wikipedia
yo
O tun lọ si TunTun Nursery and Primary School ni ilu Ikeja, ni Ipinle Eko ki o to tun wa lọ si Molly International Nursery and Primary School ni Ajao Estate fun eto-ẹkọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn náà, ó lọ sí Federal Government College, Odogbolu, Ìpínlẹ̀ Ògùn fún ètò-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀.Ufuoma ti gba oyè nínu ìmọ̀ èdè Faransé láti Yunifásítì ìlú Èkó..
wikipedia
yo
O tun ni oye giga ninu imo ọrọ ilu ati kariaye lati Yunifasiti Ilu Eko bakan naa.Ni ọdun 2011, o lọ si Ile-ẹkọ giga New York Film Academy ti o wa ni Ilu Los Angeles lati kọ ẹkọ ere ṣiṣe..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2013, ó gba oyè nínu ìmọ̀ ìṣàkóso àwọn òṣìṣẹ́ láti London Business School.Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ìdárayá gẹ́gẹ́ bi afẹwàṣiṣẹ́ ní ọdún 2000 kí ó tó tún wá lọ fún ìdíje ẹwà.ìdíje ẹwà ní ọdún 2002, ó ti kópa nínu àwọn ìdíje méjì kan..
wikipedia
yo
Ó gbégbá orókè níbi ìdíje ẹwà Miss Ebony beauty pageant ṣùgbọ́n ó gba ẹ̀bùn ti Miss Congeniality níbi ìdíje ẹlẹ́kejì, ìyẹn ti Miss Commonwealth.eré sinimá àgbéléwò ní Oṣù Kejì, Ọdún 2004, Ejenobor pinnu láti máa ṣiṣẹ́ fíìmù..
wikipedia
yo
Ó kọ́kọ́ kópa nínu eré Zeb Ejiro kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The President must not die..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kaàrún Ọdún 2005, ó kó àkọ́kọ́ ipa Olú-ẹ̀dá-ìtàn rẹ̀ nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Life and Death.Ní ọdún 2008, ó kópa gẹ́gẹ́ bi "Lillian Wright" nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ n ṣe My Mum and I.Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀àwọn àṣàyàn eré àkò Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1981àwọn òṣèré ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Eberechukwu ńwízu tí a tún mọ̀ sí Bhaira Mcwizu tàbí Bayray Mcńwízu jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O di gbajumọ lẹhin ti o gbégbá orókè nibi eto Amstel Malta Box Office (AM) elekèéta..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2009, wọ́n yàán fún àmì-ẹ̀yẹ kan ti Africa Movie Academy Awards.Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀ Cindy's Notenjg Tales of Eve Kiss and Tell (2011) calabash lies Men Tell my rich Boyfriend (2014) a lonely night cruel intentions the visit (2015) Tiwa's baCompareSawọn eré tẹlifíṣọ̀nù rẹàwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn òsèré ará Nàìjíríàọdún Ọjọ́ìbí Kòsí (àwọn ènìyàn Alààyè)Àwọn ọmọ Igbo..
wikipedia
yo
Rosaline Ufuoma Meurer (tí a bí ní 15 Oṣù Kejì Ọdún 1992), jẹ́ òṣèrébìnrin àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Gábíàbíàbíà àti Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó ti ní oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ ìṣàkóso òwò, ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ bí a ti ṣe ń ya àwòrán.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ Meurer bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi afẹwàṣiṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè Gábíàbíà, ṣááju kí ó tó wá sí Nàìjíríà ní ọdún 2009..
wikipedia
yo
Desmond Elliot ló gbàá nímọ̀ràn láti máa ṣiṣé eré ìtàgé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó dé sí ìlú Èkó níbi tí ó ti kọ́kọ́ ṣe eré kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Spellbound ní ọdún 2009 kí ó tó tún kópa nínu eré In the Cupboard ní ọdún 2011.Ní ọdún 2012, ó tún kó ipa kékeré kan nínu eré Weekend Getaway..
wikipedia
yo
Lẹhin kikopa ninu fiimu ti 2012 naa, o da iṣẹ ere sise re duro fun igba diẹ lati le raye tun tẹsiwaju ninu eko re..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ó padà sídi iṣẹ́ fíìmù rẹ̀ nígbà tí ó kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Oasis..
wikipedia
yo
Ní ọdún tí ó tẹ̀le, ó kópa nínú àwọn eré tí àkọ́lé wọn ń ṣe Damaged Petal, Red Card àti Open Marriage.Ní ọdún 2017, ó kó ipa Olú-ẹ̀dá-ìtàn nínu eré Our Dirty Little Secret..
wikipedia
yo
Ní ọdún kan náà, ó tún kópa nínu àwọn eré bíi Philip, Polycarp, The Incredible Father àti Pebbles of Love..
wikipedia
yo