cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
O pada tun kuro ni Ilu Lọndọnu pẹlu ebi rẹ lati lọ gbe ni agbegbe Scarsdale ni Ilu New York, ṣugbọn o maa n lo si orile-ede Ghana lọdọọdun lati lo awon asiko isinmi re.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí Amarteifio padà sí orílẹ̀-èdè Ghana ní ọdún 1997.. | wikipedia | yo |
Ó gba oye-ẹ̀kọ́ ninú ìmọ̀ nipa àwọn ẹ̀yà Aláwọ̀dúdú lati Ilé-ẹ̀kọ́ giga Brandeis University ni ọdún 2004.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ipari Eko, o ri iṣẹ si Ile-iṣẹ Whitaker Group, eyi ti o wa ni Washington,DC gege bi alámọ̀ràn fún Ìsókè ètò ọrọ̀-ajé Áfíríkà.Ni ọdún 2006, Amarteifio lọ sí Accra, orílẹ̀-èdè Ghana láti ṣiṣẹ́ Ìdàgbàsókè ọrọ̀-ajé.. | wikipedia | yo |
Láìpẹ́jọjọ sí ìgbà náà, ó ní ìròrí láti ṣe ìbádọ́gba eré Sex and the City ní ìlú Accra.. | wikipedia | yo |
Amarteifio padà sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láti lọ kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Georgetown University ó sì gba oyè-ẹ̀kọ́ gíga ní ọdún 2010.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó fi wà ní ìlú Georgetown, ó kẹ́kọ̀ọ́ lábẹ Mike Long, ẹnití ó gbàá níyànjú láti máa ṣiṣẹ́ ìfẹ́ ọ̀kan rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ònkọ̀tàn eré.. | wikipedia | yo |
Amarteifio gba iṣẹ́ ilé ìfowópamọ́ àgbáyé, èyí tí ó mú kí ó padà sí ìlú Accra.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn Oṣù Mélòó kan tí ó padà sí Ghana, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní fi ìròrí eré rẹ̀ tó àwọn òṣìṣẹ́ eré tẹlifíṣọ̀nù létí.. | wikipedia | yo |
Temitope Christopher ìkọ̀sẹ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Tope Nop jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ kòpò bí Tope gẹ́gẹ́ bi àkọ́bí àwọn òbí rẹ̀ sí ìlú Èkó àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ wá Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ girama tí Model College, tí ó wà ní ìlú meran ní ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
O kẹkọọ gboye akọkọ ninu imọ Mass Communication ni Ile-ẹkọ Fasiti Ipinle Eko.O ti gba opo ami-eye fun aeon ise takun takun ti o n gbe se ni inu agbo awon osere Nollyeọdún.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ì wo àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọ̀kan tí tàdes ti gbé jáde ní àwọn sinimá káàkiri ní ilẹ̀ adúláwọ̀ àti ní òkè òkun bíi Cannes Film Festival, Toronto International Film Festival àti Bfi London Film Festival.. | wikipedia | yo |
Ó jáwọ́ nínú Ìkópa nínú eré fúngbà díẹ̀ láti lè fojú sinẹ̀kọ́ rẹ̀ , lẹ́yìn tí ó sì kàwé jà, ó ṣiṣẹ́ fúgba díẹ̀ ní ilé iṣẹ́ rédíò ti UNIG FM.. | wikipedia | yo |
Tope fìgbà kan rí ṣe olóòtú ètò lórí ìkànì NTA.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, Tope tún kópa nínu eré a Solun's Story àti eré Out of Juọ̀gbẹ́ni.. | wikipedia | yo |
Ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré Suru Le're ní ọdún 2016, gẹ́gẹ́ ẹ̀dà ìtàn Kyle Steven-Adédoyin jẹ́ kí àwọn ènìyàn ó fẹ́ láti máa wo eré tí ó bá ti kópa.. | wikipedia | yo |
Tope kópa nínú eré apanilẹ́rìn kan tí wọ́n pe ojúkòkòrò àti slow Country ní ọdún 2017.Ó tún di gbajú-gbajà olùgbéré-jáde pẹ̀lú ẹrẹ̀ tirẹ̀ TY ó gbé jáde tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní What Lies Within.Ní ọdún 2018, kópa nínú eré ọ̀daràn kan tí àkọ́lé rẹ̀ n jẹ́ knock out Blessing.. | wikipedia | yo |
DÁDÁ NÍNÚ ERÉ THE lost of Okoroshi gún tún kópa nínú eré tí àkọlé rè ń jẹ́ The Ghost and the House of Truth.Àwọn iṣẹ́ mìíràn tí ó tún ń seni ọdún 2016, wọ́n fi Tope gúnp ṣe aṣojú fún ilé-iṣẹ́ Global Global Rights, Ilé-iṣẹ́ tí ó ń rí sí ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn láti lè jẹ́ kí ó lè ṣe ìpolongo tako tako ìwà ìfidiọlọ́pọ̀ àwọn ọmọ obìnrin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn àmì-ẹ̀yẹ àti ÌFISỌRÍ Bíṣọ́ọ̀bù Àṣàyàn eré rẹàwọn Eré Orí Èrò amóhùmáwòrán-Ère Orí-ìtàgé Bíṣọ́ọ̀bù Ìtọ́kasí Ijaso Ijach Film Actor Actor of Lagos alumnimale Actors from Lagos Mamale Actors of Birth Missing (Living People)Àwọn Ènìyàn Alààyèrin-Century Nigerian Malé Actors Radio personaOnídàájọ́ Radio Radio Májẹ̀múláṣẹ.. | wikipedia | yo |
Aminu Aliyu Shariff ti a tun mo si aminu Momoh ni won bi ni ojo ketadinlogun osu keji odun 1977 l, je adari ere, ònkọ̀tàn, olùgbéré-jade, ati onise ori ero amo-máwòrán, olóòtú iwe iroyin ọmọ orile-ede Naijiria.Awon aṣayan ere reaminu Shariff's filssedyacasallist of Awards received by aminu Aliyu Shariff.Awon itọkasiawon Ọjọ́ìbí ni 1977Nigerian male Film ActorsHausa-language Mass Mediàwọn ènìyàn Alààyèmale Actors in Hausa cinema-21st Nigerian male Actors.. | wikipedia | yo |
Ebori Musa, ti Voba mo si dan IBMro ti won bi ni ojo kejila osu kejila odun 1971, je ògbóǹtagí osere, alawada, olùgbéré-jade, ati adari ere Hausa, omo orile-ede Naijiria .. | wikipedia | yo |
Òun ni wọ́n ń pe ní asíwájú àti olùdásílẹ̀ agbo kannywood , ó náà tún ní ó tún mọ ìtara ṣe jùlọ nínú gbogbo àwọn òṣèré aláwàdà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣaájú kí ó papọ̀ dá ní ọdún 2014.ètò-ètò rẹ̀ ìròyìn ìrọ̀ lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti “Lásán tí ó wà ní Wàràwa, ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama “Government Teachers College" tí ó wà ní ìlú Wibùṣùn ní Ìpínlẹ̀ ní ìpínlẹ̀.. | wikipedia | yo |
O dara po mo ile-iṣẹ atunṣe awọn ẹlẹ́wọ̀n ni ọdun 1991, ti o si fise naa sile ni leyin odun die, lati dara po mo ẹgbẹ osere Tiata.. | wikipedia | yo |
Ere re akọkọ ti o kọkọ gbe jade ni 'Yar Mai ganye which promoted his career.popular Songs include olùwán naira, idi wanzami, DuReba Makaho.Early Careerbelu Musa became popular in Hausa movie cinema few years after when he joined the industry.. | wikipedia | yo |
Some of his popular movies includes Andamali, IBMro aas, Ipani angon Hajìyà, IBM Dan Fúlàní.. | wikipedia | yo |
His career as an Actor continues when he turned to be a full-time comedian and began sọin with his popular Songs such as Banan naira, Idi Wamiami, dírého Makaho.Awon Aṣa eré rèaward itọkasiàwọn Ọjọ́ìbí ní 1971àwọn Ojoaláìsí ní 2014Nigerian male film Actors Munls Mediamale in Hausa with Hausa-ọnnì Nigerian male from Kano State.. | wikipedia | yo |
Nadia Fares Anliker (tí a bí ní 18 Oṣù Kẹẹ̀sán, Ọdún 1962) jẹ́ olùdarí àti ònkọ̀tàn eré ọmọ orílẹ̀-èdè Ìjíptì àti Swítsàlandì.Itọ̀ rẹ̀ a bí Fares ní ìlú Bern, orílẹ̀-èdè Swítsàlandì.. | wikipedia | yo |
baba rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Ijipti tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Swítsàlandì.. | wikipedia | yo |
Ó kọ́ èdè èdè Lárúbáwá ní àkókò tí ó n kàwé ní ìlú Káírò, orílẹ̀-èdè Ìjíptì.. | wikipedia | yo |
O gba oye-ẹkọ lati Ile-ẹkọ giga Cairo University ni ọdun 1986.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún yìí kan náà ni Fares ṣe adarí fíìmù fún ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀, àkọ́lé fíìmù náà n ṣe Magic Binculars.. | wikipedia | yo |
Fares bẹ̀rẹ̀ sí ní lọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga New York University ní ọdún 1987 láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa fíìmù.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1991, ó gba ẹ̀bùn kan tí ààjọ Stanley Thomas Johnson Foundation gbé kalẹ̀ nípasẹ̀ fíìmù oníṣókí rẹ̀ kan táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní Sugarblues.. | wikipedia | yo |
Ní àkókò tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga New York University, Fares ṣe amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ fún Krzysztof Kiecs níbi àwọn fíìmù tí ó darí.. | wikipedia | yo |
Fares padà tún gba oyè-ẹ̀kọ́ gíga nínu ìmọ̀ fíìmù ní ọdún 1995.Ní ọdún 1996, Fares darí àkọ́kọ́ fíìmù gígùn tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Miel et Cendres.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà dá lóri àwọn mẹ́ta kan tí wọ́n ń ti ìlú kan bọ́ sí òmi.. | wikipedia | yo |
Lapapọ, fiimu naa ti gba ami-eye mejidinlogun nibi ọpọlọpọ awọn ayẹyẹ ajọdun fiimu, to fi mọ ti ẹbun Oumarou Ganda, eyi ti o gba nibi ayẹyẹ Panafrican Film and Television Festival of Ouagadougou.. | wikipedia | yo |
Doria Achour (tí a bí ní 1 Oṣù Kẹẹ̀ta, Ọdún 1991) jẹ́ òṣèrébìnrin àti olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Fránsì àti Tùnísíà.Isẹ̀mí rẹ̀ Achour jẹ́ ọmọ sí olùdarí fíìmù àti òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Tùnísíà Lotfi Achour àti ìyá tí n ṣe ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Rọ́sí́n.. | wikipedia | yo |
Arákùnrin ẹ̀gbọ́n rẹ̀ jẹ́ ònkọ̀tàn bẹ́ẹ̀ ló sì tún ní arákùnrin àbúrò.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó wà lọ́mọdé, ó maá tẹ̀lé àwọn òbí rẹ̀ ní àkókò àwọn ìgbaradì wọn fún àwọn eré wọn.Ní ọdún 2002, Achour kó ipa ọmọbìnrin Sergi López nínu eré Les femmes .... | wikipedia | yo |
Ingun les enfants d'abord ..., Èyí tí Manuel Poìrìer darí.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn kíkópa náà, Achour lọ fún àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kan ní Theatre des Déchargeurs fún ọdún kan gbákón.. | wikipedia | yo |
Ó kó àwọn ipa amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ nínú àwọn fíímù bíi l'èè naturel àti L'École pour tous.. | wikipedia | yo |
Láti gbájúmọ́ ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀, Achour dá ṣíṣe iṣẹ́ fíìmù rẹ̀ dúró fún ọdún mélòó kan.. | wikipedia | yo |
Achour gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ LÍTÍRÉṢỌ̀ láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Paris-Sorbonne University, lẹ́hìn náà ló gba oyè gíga nínu ìmọ̀ sinimá láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Paris Diderot University.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, Achour kó ipa Yasìkọ̀ròyìn nínu eré La fille publique.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2013, Achour darí àkọ́kọ́ fíìmù oníṣókí rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Laisse-moi finir, èyí tí ó dá lóri àwọn rògbòdìyàn tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní Tùnísíà lẹ́hìn ìfẹ̀hóhìn hàn àwọn ẹlẹ́ṣin Musulumi.. | wikipedia | yo |
wọ́n wo fíìmù náà níbi ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ayẹyẹ àjọ̀dún tó sì gba àmì-ẹ̀yẹ níbi ìdíje kan ti ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Iṣe takuntakun rẹ̀ nínu fíìmù La Fille publique mú kí olùdarí Sylvie Ohayon pèé láti darapọ̀ mọ́ àwọn olùkópa gẹ́gẹ́ bi Stephanie nínu fíìmù Papa was not a Rolling Stone ti ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, Achour kó àkọ́kọ́ ipa rẹ̀ lédè Lárúbáwá nínu fíìmù Burning Hope.. | wikipedia | yo |
Ó tún darí fíìmù oníṣókí tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Le reste est l'óuvre de l'otta, èyítí ó gba àmì-ẹ̀yẹ níbi ayẹyẹ Sundance Film Festival ti ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
ọ̀tà-dá Abdi (tí a bí ní 25 Oṣù Kẹẹ̀wá ọdún 1970) jẹ́ olùdarí eré àti agbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Ethiópíà.Itọ̀ rẹ̀ a bí Abdi ní ìlú Dire Dawa ṣùgbọ́n ó gbé ní ìlú Addis Ababa títí tí ó fi pé ọmọ ọdún mẹ́rin.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn ìfipáyí ètò ìjọba tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 1974, ìyá rẹ̀, tí ó ti pínyà pẹ̀lú bàbá rẹ̀, sá lọ sí ìlú Nairobi ní orílẹ̀-èdè Kẹ́nyà pẹ̀lú rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Abdi parí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama rẹ̀ ní Kenya.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún 17, ó kó lọ sí Kánádà pẹ̀lú ẹbí rẹ̀, níbití ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ ìṣòwò ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga University of Western Ontario.. | wikipedia | yo |
Ó rí ararẹ̀ yàtọ̀ sí ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ tí wọ́n fẹ́ láti wá iṣẹ́ sí Wall Street lẹ́hìn ìparí ẹ̀kọ́ wọn.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn ìparí ẹ̀kọ́ Abdi, ó ṣiṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún gẹ́gẹ́ bi oníṣẹ́ ìròyìn àti bíi agbéréjáde.Ní àwọn ọdún 1990, Abdi pàdé Bernardo HataLucci ní ìlú Nepal, ẹnití ó n gbé ìgbéṣẹ́ lọ́wọ́ láti gbé eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Little Buddha jáde.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2001, Abdi padà sí orílẹ̀-èdè Ethiópíà ó sì darí àkọ́kọ́ fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The River That Divides, tó n ṣe àyẹ̀wò ìgbésí ayé àwọn obìnrin Ethiópíà ní àkókò ogun Eritrean-Ethiopian.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà gba àmì-ẹ̀yẹ fún ti fíìmù tó dá lóri ẹ̀tọ́ ọmọènìyàn.Abdi tún ṣiṣẹ́ agbéréjáde.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2001, ó gbé fíìmù oníṣókí kan jáde táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní The Father latọwọ Ervants Woldeamland.. | wikipedia | yo |
Abdi ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Abderrahmane Sissako gẹ́gẹ́ bi agbéréjáde àti aṣàpẹrẹ aṣọ níbi àwọn fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé wọn ń ṣe Waiting for Happiness (2003) àti Bamako (2006).. | wikipedia | yo |
Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi ọ̀kan lára àwọn ìgbìmọ̀-onígbẹ̀ẹ́jọ́ fún fíìmù oníṣókí níbi ayẹyẹ àjọ̀dún <i>Cannes Film Festival</i> ti ọdún 2013.. | wikipedia | yo |
O se igbeyawo pelu Sissako.Awon itọkasiawon ìtàkùn ìṣẹ́gun -da Abdi at the Internet Movie Databaseàwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ni 1970.. | wikipedia | yo |
Chidinma ati Chidiebere anèké jẹ́ gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ìbejì tí wọ́n jọ ara wọn lọ́pọ̀lọpọ̀ nínú ẹgbẹ́ Nollywood tí wọ́n máa ń pè ní ìbejì Anèké.. | wikipedia | yo |
Wọ́n jẹ́ àbígbẹ̀yìn àwọn òbí wọn àti ọmọ bíbí ìlú ìpínlẹ̀ Enugu lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ wọn láti ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí Chidinmma àti Chidie lọ́jọ́ kẹfà oṣù kẹjọ ọdún 6 1986 ní ìpínlẹ̀ Enugu, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ọmọ ilé-olórogún oníyàwó mẹ́ta níwọ̀n.. | wikipedia | yo |
Baba wọn jẹ́ olówó ati ọlọ́rọ̀ tí ó fi owó ati ọlá kẹ́ wọn láti ìgbà èwe wọn, ṣugbọn èyí yí pada ní kété tí baba wọn ṣaláìsí, tí àwọn ẹbí sin pín ogún rẹ̀ láàárín ara wọn.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ wọn ní ìpínlẹ̀ Enugu kí wọ́n tó tẹ̀ síwájú ẹ̀kọ́ gíga ní University of Nigeria, Nsúmọ́ níbi tí wọ́n ti kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ètò ìbánisọ̀rọ̀ àti ìmọ̀ ìfowópamọ́ àti ìṣúná-owó lọ́tọ̀ọ̀tọ̀.Iṣẹ́ àwọn ìbejì ánèké bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1999, tí wọ́n sì kópa àkọ́kọ́ nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Ẹnúka.. | wikipedia | yo |
Sinimá yìí ló mú ògo wọ́n bù yọ lágbo òṣèré sinimá àgbéléwò Nollywood.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2004,àwọn ìbejì wọ̀nyí tún kópa nínú gbankọgbì sinimá kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Desperate Twins, èyí mú kí wọ́n gbajúmọ̀ sí i, tí wọ́n sin yàn wọ́n mọ́ àwọn tí wọ́n díje fún òṣèrébìnrin tí ìràwọ̀ wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní tan lórí The African Magic Viewers' Choice Award.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ náà àwọn ti gbé oríṣiríṣi sinimá jáde fún ara wọn.. | wikipedia | yo |
Lara awon sinima won mi; 'Heart of Isiaku', 'Ónòcs', 'broken Amtireon’’, ati 'Adaora'.àṣàyàn awon sinima won Yorale FriendsDesperate TwinsLagos Girlsbroken Amonaonayẹ humanics Awardàwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Nobasa Kupi Manaka (tí a bí ní ọdún 1962) jẹ́ oníjó àti òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Gúúsù Áfríkà.Ise rẹ̀ a bí Manaka ní ọdún 1962 ní Orlando, agbègbè Sòwẹ́tò ní ìlú Johannesburg.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn tí ó ní àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ijó jíjó, òun náà maá n ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn ẹlomiran ní ilé-ìṣeré Fundad Center, èyítí ọkọ rẹ̀ tí n ṣe Matsemela Manaka dá sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1989, ó kópa nínu eré kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Gorée.. | wikipedia | yo |
Eré náà dá lóri arábìnrin kan tí ó rin ìrìn-àjò lọ sí abúlé Gorée ní ibi tí ó ti pàdé ìyáàgbà kan tí ó ń ṣe àlàyé fún nípa àgúngúnbá rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilẹ̀ Áfríkà.Ní ọdún 1991, Manaka dá ìwé ìròyìn kan sílẹ̀ tí ó wà fún ọ̀rọ̀ nípa ijó tí àkọ́lé rẹ̀ n ṣe Rainbow of Hope, ó sì tún ṣẹ̀dá àwọn ijó tó fi mọ́ èyítí wọ́n jọ nínú eré Daughter of Nebo ti ọdún 1993.. | wikipedia | yo |
Nibi awon ijo ti o ṣẹda, o gbiyanju lati ri wipe awọn ijo naa ṣafihan awọn asa ilẹ Afrika ni ibamu pẹlu awọn ilana ijó ti igbalode.. | wikipedia | yo |
Ó pàdánù ọkọ rẹ̀ ní ọdún 1998 nínu ìjàba ọkọ̀.Ní ọdún 2010, Manaka kópa nínu eré oníṣókí kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Exiled èyí tí Tiisetso Dladla ṣe adarí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní àkókò àwọn ọdún 2010 sókè, ó ń gbé pẹ̀lú akọrin Hugh Masekela, ẹnití ó ní àrùn jẹjẹrẹ.. | wikipedia | yo |
Oun fúnrarẹ̀ naa ti ṣe ayẹwo ni ọdun 2016 ti wọ́n sì ti jẹ́ kí ó mọ̀ pé ó ní àrùn jẹjẹrẹ.. | wikipedia | yo |
Hugh Masekela pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ ní Oṣù Kíní Ọdún 2018, ṣùgbọ́n ará tirẹ̀ padà sípò lẹ́hìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ oṣu tí ó fi ní ìtọ́jú.. | wikipedia | yo |
Ní àkókò ìtọ́jú rẹ̀, Manaka ní ìròrí láti ṣètò eré ijó kan tí ó pè ní Dancing Out of Cancer láti fi wá owó fún àwọn tí ó ní àrùn jẹjẹrẹ.àwọn Ìtọ́kasíàwọn ààwọn ìjáde kòbá Manaka at at the Internet Movieàwọn ènìyàn ènìyàn Alààyè Ọjọ́ìbí ní 1962.. | wikipedia | yo |
Mercy èké jẹ́ oṣere, onijo ati onisowo lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó gbé igbá orókè níbi ìdíje Big Brother Naija ti apá kẹ́rin tí wọ́n ṣe ní oṣù kẹwàá ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kẹrìnlá osù kẹta ọdún 2020, ó gba àmì ẹ̀yẹ obìnrin tó dára tí ó dára jù lọ níbi ayẹyẹ Africa Magic Monv's Choice Award.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ èké jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ ìmọ́.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé Èkó gbugbu Girls Secondary School ní ìlú Owerri.. | wikipedia | yo |
Ó gboyè jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti ìmọ̀ State University ní ọdún 2014.Iṣẹ́ Èké darapọ̀ mọ́ Ìdíje Big Brother Naija ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2020, ó yàn nínú eré Alakadá, èyí sì ní eré tí ó má kọ́kọ́ ṣe.. | wikipedia | yo |
O farahan gege bi onijo ninu ere orin baby Mama eyi ti Davido ati Ichaba gbe kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Èké jẹ́ AmBase fún Ciroc àti Mr Taxi.Ami Eye tí ó ti Gbàáwọ́n Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Latefa Ahrar (tí a bí ní 12 Oṣù kọkànlá Ọdún 1971) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Mòrókò.Isẹ̀mí rẹ̀ a bí Ahrar ní ìlú Meknes.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré tẹlifíṣọ̀nù rẹ̀ pẹ̀lú kíkópa nínu eré Bent Luchoẹgbẹ̀rún latọwọ Ablatif Ayachi ní ọdún 1990.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn náà, ó lọ ilé-ẹ̀kọ́ Institut supérieur d >art dramatique et d'animation Culturelle (IsaFDA) níbití ó ti gboyè ní ọdún 1995.. | wikipedia | yo |
Láti ìgbà náà, ó ti ṣe àwọn eré ìpele àti sinimá àgbéléwò, ó sì ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àmì-ẹ̀yẹ fún àwọn iṣẹ́ takuntakun rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ahrar ṣàlàyé pé òun fẹ́ràn láti máa kó àwọn ipa tí ó ní ìpèníjà, bẹ́ẹ̀ kò sì gbádùn láti máa ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú oríṣiríṣi àwọn olùdarí eré láti mú ìdàgbàsókè bá iṣẹ́ òṣèré rẹ̀.Láti ọdún 2005 sí 2008, Ahrar kópa nínu eré La derni nuit tí ààjọ Institut du monde arabe gbé kalẹ̀ ní ìlú Paris.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2008, ó kópa nínu fíìmù méjì kan tí àkọ́lé wọn ń ṣe Une Fami Emprun àti Les victimes .. | wikipedia | yo |
Ninu fiimu akọkọ, o ko ipa apanilẹ́ẹ̀rín kan gẹ́gẹ́ bi ọ̀rẹ́bìnrin Mouna Fetu, ṣugbọn gege bi iyawoole ti o ni awon omo meta ninu fiimu ekeji.Ni odun 2009, o kopa ninu ere Eduardo De Filippo kan ti akole re je Douleur sous clé, eyiti won tumọ si ede Mòrókò, pẹlu ajọṣepọ Hicham Ibrahimi ati Henri Thomas.. | wikipedia | yo |
Atúmọ̀ èdè náà jẹ́ Abdellatif Firdaous tí olùdarí sì jẹ́ Karim Troussi.eré rẹ̀ kan tí àkọ́lé rẹ̀ n ṣe “kafar Naoum” fa ariyanjiyan nitori wíwọ Sokoto péńpé rẹ̀ ninu eré naa, èyítí ó mú kí àwọn ẹnìkan dẹ́rùbaa pẹ̀lú ijiya iku.. | wikipedia | yo |
Sophie Rammal Alakija (Bii ní ọjọ́ keje osù keji ọdún 1994) jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa tí ó kó nínú eré Haita àti Assistant Madamiìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bí Alakija ní ọjọ́ keje osù kejì ọdún 1994 sí ìdílé Mùsùlùmí.. | wikipedia | yo |
O jẹ ololufẹ fun gbajumọ olorin, Wizkid lati ọdun 2010 di ọdun 2016.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣe igbeyawo wọn ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2016 ní ìlú Surulere ní ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Ó sì bí ọmọ meji.Iṣẹ́ ni igba tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹrindinlogun, ó kópa gẹ́gẹ́ bí oníjó ninu eré ọ̀rìn Holla at Your Boy èyí tí Wizkidgbé jáde.Ó ti kópa nínú oríṣìíríṣìí eré bíi drawing Stds, Getting Over him, àti small Chops.. | wikipedia | yo |