cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ó tẹ̀síwájú láti gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ ìmaaDanidòfo ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Àmọ́dù Bello ṣááju kí ó tó tún wá gba oyè-ẹ̀kọ́ míràn nínu ìmọ̀ ẹ̀sìn Kristẹni láti Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ Caroline King ń gbé lọ́wọ́lọ́wọ́ ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ó sì ti di Aladelórí pẹ̀lú fífẹ́ Captain Kọ́láwọlé King, ẹnití ó ti bí ọmọ mẹ́ta fún.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré Carol bẹ̀rẹ̀ nígbà kan tí ó fi lọ fún àyẹ̀wò eré Rédíò kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ I Need to Know ṣááju kí ó tó tẹ̀síwájú láti kópa nínu eré Everyday People.. | wikipedia | yo |
Ó kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìpele àti àwọn sinimá àgbéléwò tó fi mọ́ Dazzling Mirage, Pásítọ̀ Dedèdèdè àti The Gods Are Still Not To Blame.. | wikipedia | yo |
Fún ipa rẹ̀ láti mú ìpàdé ìbá agbo eré sinimá ṣíṣe, wọ́n yẹ́ Carol sí pẹ̀lú àmì-ẹ̀yẹ "African Youth Role Model Award" ní ọdún 2009.àṣàyàn àwọn eré àko eré tẹlifíṣọ̀nù I Need To Know Everyday People Tinsel Everyday People Edge of Paradise Blaze of Glory Eko Law Emerald Skinny Girl in Transite ìpele V Monologues Ajayi Crowther Five Maidens Maidẹs of Fadaka Chronicles The Wisse The sinimá àgbéléwò National Deval Dazzling Mirage FI N Colored Girls The Gods Agbòǹgbò Not TO Mi Sou TO To Wúrà North Ẹ Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Agbihan ní 1963 ní 1963 ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Folake akínyẹmí ti won bi lọjọ kokandinlogbon osu keta odun 1999 (31 March 1990) je gbajumo a sare-ije fun orile-ede Norway, sugbon ti o je omo bibi Ipinle Eko ni orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
O jẹ́ gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká eléré ìwọ̀n mita ọgọrun-un ati igba.Ìgbésí ayé iṣẹ́ rẹ ni ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí Folake sí ìlú Èkó.. | wikipedia | yo |
Olubala awọn ọ̀jẹ̀ wẹ́wẹ́, o gbe ipo kẹrin ninu eré sísá iwọn mita ogorun-un nibi idije 2007 European Youth Olympic Festival, ati nibi idije 2009 European Junior Championships.. | wikipedia | yo |
O gba ipo keji ninu ere ije oníwọ̀n ogorun-un, ọsin gbe ipo kẹfa ninu ere ìjẹ oníwọ̀n igba.. | wikipedia | yo |
Bakan naa, o dije lodun 2006 ninu idije relay Only), The 2007 European Junior Championships, ati idije 2008 World Junior Championships in Athletics – Women's 100 metres ninu ìdíje oníwọ̀n mita ogorun-un ati 2008 World Junior Championships in Athletics – Women's 200 metres onídu mítà igba, bẹ́ẹ̀ náà lọ́dún 2011 ó kópa nínu 2011 European Athletics U23 Championships – Women's 100 metres àti 2011 European Athletics U23 Championships – Women's 200 metres) onídu mítà ọgọ́rùn-ún àti igba, ṣùgbọ́n kò pegedé fun asekagba Without.Fún ìdíje ìpele àwọn àgbà, ó kópa nínú 2009 European Indoor Championships, 2010 World Indoor Championships, 2010 European Championships, 2012 European Championships àti 2013 European Indoor Championships láì pegede fun asekagba.. | wikipedia | yo |
Nínú ìdíje láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tó ti kópa gbẹ̀yìn, ó dé ìpele tó tẹ̀lé àṣekágbá nínú ìdíje Athletics at the 2013 Summer Universiade - Women's 100 metres oníwọ̀n ọgọ́rùn-ún ti 2013 Summer Universiade.. | wikipedia | yo |
Àwọn àkókò ìsáré rè tó yára jù ìṣẹ́jú àáyá 7.36 Nínú ìdíje ìwọ̀n ọgọ́ta (60),èyí wáyé lọ́dún 2009 ní flọ́rọ̀; ìṣẹ́jú àáyá 11.46 nínu ìdíje oníwọ̀n ọgọ́rùn-ún mítà (100),lọ́dún 2012 ní ìdíje ní flọ́rọ̀; àti àáyá 23.61 nínú ìdíje oníwọ̀n mítà ìgbà,lọ́dún 2010 ní Donnas, Italy.. | wikipedia | yo |
She represented the clubs il I bul and sk Vidal before 5D ik tjalve ahead of the 2014 Season,àwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Alexandra López, tí a mọ̀ sí Alex López jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè Brasil tí ó jẹ́ afẹwàṣiṣẹ́ tẹ́lẹ̀rí.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa kan tí ó kó nínu fíìmù Amejolọ́wọ́ kan táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní Domitila 2.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1993, ó ṣe ipò kejì níbi ìdíje ẹwà, Most Beautiful Girl in Nistabẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ a bí López ní ìlú Jọs ṣùgbọ́n ó dàgbà ní ìlú Obo, Ìpínlẹ̀ Anámbra ní gúúsù ìla-òòrùn Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni àbílé kejì àwọn ọmọ márùn-ún ti àwọn òbí rẹ̀.Iṣẹ́ rẹ̀ López ti ṣàfihàn nínu eré Faper Láboki kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Changing Faces níbití ó ti kó ipa Franca.. | wikipedia | yo |
Ó tún ti kó àwọn ipa olú-ẹ̀dá-ìtàn àti ipa amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ nínu àwọn fíìmù Nollywood bíi Domitilla, Love, Sex & Marriage, Dangerous Girls, Abuja Connection 2&3, Emotional Hazard, The One I Love, Akata, Catastrophe, Jungle Justice, Moving Train, Remarkable Pains, Scout, Sisters On the Run, Six Problem Girls, àti The Good The Bad And The Terrible and Walls Have Ears .. | wikipedia | yo |
Ó kó ipa ìbálòpọ̀ ẹlẹ́yàkannáà nínú Domitilla.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ López kòi tíì ṣe ìgbeyàwó ṣùgbọ́n ó ti ní ọmọkùnrin kan.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Keèje Ọdún 2013, a gbọ́ wípé López àti Slim Burna, akọrin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó wà ní ìlú Port Harcourt, dì jọ n ṣe wọléwọ̀de, ṣùgbọ́n àwọn méjéèjì fèsì pé ọ̀rẹ́ lásán làwọn jẹ́.Àwọn àṣàyàn eré àko Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn òṣèré ará Nàìjíríàọdún Ọjọ́ìbí Kosi (àwọn ènìyàn Alààyè | wikipedia | yo |
Uche Mac-Auley (tí àbísọ rẹ̀ jẹ́ Uchechukwu NwaneAmaka ) tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ bi Uche Obi Osotule jẹ́ gbajúgbajà òṣèré, ònkọ̀wé, olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ Mac-Auley wá láti Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà ní Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí Mac-Auley jẹ́ olùkọ́ tí wọ́n sì máa ń ṣiṣẹ́ káàkiri.. | wikipedia | yo |
Nítorí ìdí èyí, Mac-Auley kò gbé lójú kan fún ìgbà pírú.. | wikipedia | yo |
Èyí mú kí Mac-Auley lọ sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ṣùgbọ́n ó padà parí ní ilé-ìwé Osoro Primary School, ó sì lọ sí Anglican Girls Grammar School àti Idia College fún ètò-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Mac-Auley gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Delta State University.Iṣẹ́ rẹ̀ a lè ṣàpèjúwe Mac-Auley bí gbajúgbajà òṣèré àti ọ̀kan nínu àwọn ẹni ìṣaájú ní agbo eré sinimá ti Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Mac-Auley ṣe àkọ́kọ́ ìfihàn rẹ̀ lágbo eré sinimá ti Nàìjíríà pẹ̀lú kíkópa gẹ́gẹ́ bi "Nkemji" nínu eré tẹlifíṣọ̀nù kan ti ọdún 1991 tí a pe àkọ́lé rẹ̀ ní Checkmate, èyítí Amaka Igwe ṣe àgbékalẹ̀ àti dídarí rẹ̀, ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn òṣèré Nollywood bíi Richard Mofe-Damijo, Norbert Young, Francis Agu, Bimbo Manuel, Kunle Bamte, àti Binta Ayo Mogaji.. | wikipedia | yo |
Mac-Auley ní ìsinmi ọlọ́jọ́gbọọrọ nídi iṣẹ́ òṣèré láti máa kọ ìwé ìtàn fún àwọn ọmọde, ṣùgbọ́n ó padà sí ìdí iṣẹ́ òṣèré ní ọdún 2016 nígbàtí ó kópa nínu fíìmù kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Mid-Life.yàtọ̀ sí ṣíṣe iṣẹ́ òṣèré, Mac-Auley tún jẹ́ ònkọ̀tàn àti agbéréjáde, ó sì ti ní lórúkọ rẹ̀, àwọn fíìmù bíi; Dangerous Twins, Sins of my Mother àti in a Lifetime.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ Mac-Auley ti ṣe ìgbeyàwó lẹ́ẹ̀mejì ri.. | wikipedia | yo |
Ní àkókò pẹ̀lú olóòtú Obi Osotule, ẹnití ó pàdé ní ọdún 1993 nígbà tí wọ́n fi n gbáradì fún eré UnFor Sin.. | wikipedia | yo |
Francis Agu tàbí Francis Okechukwu Agu jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé sinimá àti orí ẹ̀rọ ìhùyàn-máwòfẹ́ ọmọ ń orílẹ̀-èdè Nàíjíríà tí wọ́n bí ní ọ̀jọ̀lá lálá Oṣù kejì ọdún 1965.. | wikipedia | yo |
ó di ìlú-mọ̀ọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kọ́ ní eré onípele àtìgbà-dègbà tí wọ́n ṣe àfihàn rẹ̀ ní orí ẹ̀rọ amóhùmáwòrán-máwòrán tí wọ́n pe àkòrí rẹ̀ ní Checkmateìbẹ̀rẹ̀. Àyè àti ẹ̀kọ́ rẹ̀wọ́n bí Francis ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejì ọdún 1965, sínú ẹbí ọ̀gbẹ́ni fèdèlis àti aya rẹ̀ Virginia Agu tí wọ́n jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Wnugu-gúgú ní ìpínlẹ̀ Enugu òun sì ni àbíkẹ́yìn àwọn òbí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
ó kẹkọ ní Ilé-ẹkọ́ Ldi-lálá Institute ni ilu Alagomeji ni agbègbè Èbúté-mẹta ní ìpínlẹ̀ Èkó O lọ si Ile-ẹkọ ti St.. | wikipedia | yo |
Dennis Joseph Setittery sì tọ́ dàgbà tí ó jẹ́ olùdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ náà.. | wikipedia | yo |
Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó níbi rí ó ti kọ́ nípa ìmọ̀ ìru ọ̀pọ̀ ènìyàn sọ̀rọ̀.Iṣẹ́ reagu bẹ̀rẹ̀ eré orí-ìtàgé ní inú ilé Ìjọsìn wọn bí ó tile jẹ́ wípé ó ti ń bá ilé-iṣẹ́ ìfowó-pamọ́ Arab Bank ṣíṣe nígbà náà.. | wikipedia | yo |
Àkókò eré tí Agu yóo kópa níbẹ̀ ni wọ́n pe àkọlé eré tí James Ene Henshaw kọ ti Isaac John sì gbé jáde tí wọ́n pe àkọlé eré náà ní This is our Chance.. | wikipedia | yo |
Awon ere miiran tun ni The Gods Are Not to Blame ti Ola Rotimi ko, ati Trials of Brother Obere, Ere ti ojogbon wole Soyinka se akosile re.gbaju-gbaja adari ere Segun osere dari dari ere kan ti Agu ti kopa ti o pe ni the man who never died.. | wikipedia | yo |
Orísirísi eré tún ni Agu ti kópa pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn lààmì-laaka òṣèré bí 1988 Mike.. | wikipedia | yo |
Agu tún kópa ninu eré onípele àtìgbà-dégbà Checkmate níbi tí ó ti kópa gègé Benny, ní ọdún 1990.. | wikipedia | yo |
Ó tún kópa gẹ́gẹ́ bi ichie million nínú eré tí wọ́n pe akọlt rẹ̀ ní "Living in Bondage", eré yí mi ó sì sọọ́ sí ìlú-mọ̀ọ́ká ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Agu gbe ere akoko tire jade ni odun 1994 ti o pe akole re ni Jeila, o tun gbe awon ere miiran ti o tun dari awon ere naa pelu.. | wikipedia | yo |
Lára wọn ni in the name of Father, Love and 1990, a Deres call, the boy is Mine, body and Soul, a dance in the forest ati take me to Jesus.. | wikipedia | yo |
Ikú rẹagu ṣe àìsàn ní inú oṣù kẹwàá ọdún 2006, ó sì papò dà ní inú ogúnjọ́ oṣù kẹta ọdún 2007. | wikipedia | yo |
Awon asayan ere re Living in Bondage (1992) brothers 2a Minute to miduntouchableble of Dode (1993) Blood Money (1997)Àwọn Ìtọ́kasí, Newspaper Website sún News, Archive of newspaper articlethe National, Archive of newspaper Websiteìtàkùn ìjásóde Archive of Francis Agu Memorial Websiteawon Ọjọ́ìbí ni 1965awon Ojoaláìsí ní 2007Igbo Malé Actors Film film Actors Tísan From LST Of Lagos Ibidu Nigerian Malele Actors Actors Actors Salav-Century Nigerian Male Actors Àjàpá Actors lati Malelé Actors National to ọ̀gọ (1] Ni To lati Iroko ( The Ìtọ́kasí ni Ọjọ́ìbí * ** *** * lati 2020 - má Kínní lati Oku - (1993 & W | wikipedia | yo |
Annie Macaulay-Idibia (tí a bí ní 13 Oṣù kọkànlá ọdún 1984) jẹ́ afẹwàṣiṣẹ́ àti òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yàán fún àmì-ẹ̀yẹ ti òṣèré amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó dára jù níbi ayẹyẹ Best of Nollywood Awards ti ọdún 2009.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bi Annie ní Ibadan ṣùgbọ́n ó wá láti ìlú Eẹ̀ké ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom.. | wikipedia | yo |
O ko lo si ilu Eko pelu iya re lehin ipinya laarin awon obi rẹ.. | wikipedia | yo |
O ni oye-ẹkọ ninu imọ Kọmputa Iweyẹn ati Ere Tiata, eyi ti o gba lati ile-iwe giga Yunifasiti ipinlẹ Eko ati Yunifasiti Ilu Eko.Iṣẹ iṣe rẹ ṣaaju ki Annie Macaulay-Idibia to bẹrẹ iṣẹ oṣere rẹ, o ti dije nibi Queen of All Nations Beauty Pageant nibiti o ti ṣe ipo keji, o si tun ti han ninu orin kan ti 2face Idibia ti akọle rẹ jẹ African Queen.O di gbajumọ nidi iṣẹ oṣere rẹ ni Nollywood leyin kikopa ninu awọn sinima táa pe akole won ni pleasure and Crime ati Blackberry Babes.Àwọn Aṣayan ere rẹ First Family Family And Crime White White Blackpel Black Babes Return of Blackberry Babes Runs UnṢàṣà Obiageli The Sex Machine Morning After Dark Beautiful Mostero Ayeroro Aye Annie Macaulay – Idibia ti ṣe igbeyawo pẹlu 2face Idibia to si ti bi ọmọ meji fun.. | wikipedia | yo |
O bi ọmọ akọkọ rẹ, ọmọbinrin ti orukọ rẹ jẹ Isabella Idibia, ni Oṣu kejila ọdun 2008 ati ọmọ ekeji ti orukọ ti oun n ṣe Olivia Idibia ni Oṣu Kini, ọdun 2014.. | wikipedia | yo |
Ó ní ilé ìsọ kan ní ìlú Atlanta tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ "BeOlive Hair Studio".Àwọn ìyẹ́sí rẹàwọn Ìtọ́kasí àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Adenrele sônàrí jẹ́ gbajúmọ̀ oníṣòwò àti atọ́kùn nǹkan Akinṣèṣè àti iṣẹ́-ọnà.. | wikipedia | yo |
Òun ni olùdáa, ilé-iṣẹ́ iṣẹ́-ọnà, relé Art Gallery tí ó wà ní Military Street, Onikan, erékùṣù Èkó, ní ìpínlẹ̀ Èkó lọ́lẹ̀.. Nàìsàn.. | wikipedia | yo |
Òun ni olórí atọ́kùn ìṣèjìní fún tó sojú Nàìjíríà LỌ́DÚN 2017 níbi Ìpàtẹ Venice Bínna ẹlẹ́kẹ́taèdèèdè Adenrele Adedúńbú kàwé gboyè gboyè dì àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ ìṣirò-ọwọ́ ní Howard University, lẹ́yìn èyí, ó ṣiṣẹ́ ní Pricehouse Gómìnà bí Akò Akò-án fún ọdún mẹ́rin.. | wikipedia | yo |
O kawe gboye ma ninu imo Multimedia Communications ni ile Eko, Academy of Art University, bẹẹ o ni iwe eri ninu imo atọkun igbàgbọ́ ati iṣẹ-ọna lati University of the arts London.Ile ìpàtẹ iṣẹ-ọna relé bi o ṣe pada si Naijiria, o da ile ìpàtẹ iṣẹ-ọna silẹ, ti o pe ni relé Art Gallery lodun 2010, ile-iṣẹ ko bẹrẹ iṣẹ afi ọdun 2015,ti o sese fi lole gan-an.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2011,nígbà tí ó gbèrò ìdásílẹ̀ ilẹ̀ yìí, ó gbà á lẹ́rọ̀ láti dà á sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Yunifásítì ní Nàìjíríà, tí yóò pè ní;The Modern Day School of the Arts.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ilé ìwé fún àwọn olólùfẹ́ iṣẹ́-ọnà, tí yóò máa wá dàbíra ẹ̀bùn iṣẹ́ wọn.”Ìpàtẹ Venice bínna ẹlẹ́kẹtadínlọ́gọ́ta lọ́dún 2017, sọ́nàrírí ní ó darí ikọ̀ àwọn atọ́kùn auṣè ti Nàìjíríà ní ìpàtẹ Venice bínna ẹlẹ́kẹtadínlọ́gọ́ta.. | wikipedia | yo |
Eni tí ó kòwá rẹ̀ ní agbá òkọ̀wé àti aṣelámèyítọ́ iṣẹ́-ọnà, Emmanuel ìdùbúma gẹ̀gẹ̀ ní igbákejì atọ́kùn.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ náà ló wà lára àwọn adarí àṣà lọ́dún 2016 and 2017.. | wikipedia | yo |
Lóṣù kẹ́ta ọdún 2017, wọ́n yàn án lára àwọn ọgọ́rùn-ún amóríyá obìnrin ní Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ asọ̀rọ̀ ní ètò TED, bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ adájọ́ ètò ìdíje Kabe'Art bínna tó wáyé lọ́dún 2018.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ti fìgbà kan fi àwòrán rẹ̀ ṣe olú-àwòránt fún ìwé ìròyìn olóṣooṣù (Guardian Life Magazine) ní Nàìjíríà .Lọ́dún 2018, Ilé Iṣẹ́ Vogue Dárúkọ rẹ̀ mọ́ àwọn "Five Coolest Women in Lagos"Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Tayánna (ọjọ́ 29 September 1984, Chernivtsi (Ìṣọ̀kan Sofietí)) jẹ́ olórin ọmọ ilẹ̀ YuReinra.Àwọn Ọjọ́ìbí ni 1984.. | wikipedia | yo |
William Sanderson (January 10, 1944) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Samantha Biffot (tí a bí ní ọdún 1985) jẹ́ ònkọ̀tàn eré, olóòtú àti olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè-Gàbọ̀n àti orílẹ̀-èdè Faransé.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ a bí Biffot ní ìlú Parisi ní ọdún 1985.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ aláṣà púpọ̀ nítorí lilo igba èwe rẹ̀ ní àwọn ìlú bíi Gàbọ̀n, gúúsù àti gúúsù àti Fránsì, èyí tí ó padà nípa lóri ṣíṣe iṣẹ́ òṣèré rẹ̀..Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ìwé École Super Dlan Réalielle, ìyẹn Audioelle, ìyẹn ní ìlú Párì ó ti gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ sinimá ṣíṣe ní ọdún 2007.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn ìparí ẹ̀kọ́ rẹ̀, Biffot tún lọ kọ́ṣẹ́ bí àti ṣe ń ṣe eré tẹlifíṣọ̀nù àti sinimá àgbéléwò ní orílẹ̀-èdè Fránsì bákan náà.. | wikipedia | yo |
Biffot padà sí orílẹ̀-èdè Gàbọ̀n ní ọdún 2010 níbi tí òun pẹ̀lú Pierre-Yunifásítì Ceccal Dical tí dìjọ dá ilé-iṣẹ́ agbéréjáde kan sílẹ̀ táa pè ní “Princesse Production ní ọdún 2011, ó ṣètò àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún eré kíkọ, ṣíṣe olóòtú àti yíyà àwòrán eré Lásìkò ayẹyẹ International Festival of School courts tí ó wáyé ní ìlú Libreville .ní ọdún 2013, eré tẹlifíṣọ̀nù rẹ̀ kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ l'ẹ́ilil de la Cite (The Eye of the City) gba àmì-ẹ̀yẹ fún eré tẹlifíṣọ̀nù tí ó dára jùlọ ní ilẹ̀ Afirika níbi ayẹyẹ Panafrican Film and Television Festival of Ouagadougou.. | wikipedia | yo |
Eré náà dá lóri àwọn ìwà òrúórún àti àwọn pékílà tí ó ń dá sáàrin àwùjọ.. | wikipedia | yo |
Ó sọ di mímọ̀ wípé eré náà jẹ́ láti fi ṣe ìbádọ́gba eré Amẹ́ríkà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Tales from the Crypt.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, Biffot ṣe àgbéjáde The African Who wanted to fly, tó dá lórí ìgbésí ayé Luc Bendza, ògbóǹtarìgì oní Kung Fu ní orílẹ̀-èdè Gabon.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà gba àmì-ẹ̀yẹ eré-onítàn tí ó dára jù níbi ayẹyẹ Burundi International Film and Audiovisual Festival ti ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
Angela Aquereburu (tí a bí ní 11 Oṣù Kíní Ọdún 1977) jẹ́ ònkọ̀tàn, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Tógò.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ Aquereburu ni a bí ní Togo sí ọwọ́ ìyá tí ó wá láti Guadeloupe, orílẹ̀-èdè Faransé.. | wikipedia | yo |
Ó lọ ilé-ìwé ní Togo àti Pointe-a-pitre ní Guadeloupe, ṣaájú kí Kín.. | wikipedia | yo |
Ó tó gbéra lọ sí ìlú Paris láti tún lọ kẹ́kọ̀ọ́ gíga ní ilé-ìwé EsCP Business School.. | wikipedia | yo |
Aquereburu ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú òṣèrékùnrin Jean-Luc Rabatel.. | wikipedia | yo |
O ti n ṣiṣẹ iṣakoso awọn oṣiṣẹ fun ọpọlọpọ ọdun.. | wikipedia | yo |
Ṣugbọn ní ọdún 2008, ní àkókò ìgbà tí ó fi wà fún ìsinmi ní orílẹ̀-èdè Togo, o ṣakiyesi pe ẹya ere Telifisonu kan ni wón maa n se ni Ilu Togo, oun pẹlu ọkọ rẹ sii wòye si ẹya miran, eyi ti o da lori ọ̀kadà wíwà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún tí ó tẹ̀le, Aquereburu àti ọkọ rẹ̀ kó lọ sí ìlú Lomé láti máa gbé níbẹ̀, wọ́n sì dá ilé-iṣẹ́ Yobo Studios sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀yà eré tẹlifíṣọ̀nù míràn tí wọ́n gbèrò jẹ́ ipilẹ̀ fún eré Zem ti Canal àti Afrique dì jọ ṣe olóòtú rẹ̀.Aquereburu tún ti ṣiṣẹ́ lóri eré Palabre.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, ó ṣe àgbékalẹ̀ ètò tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Hospital IT, èyítí ó dá lóri Lila àwọn èyàn lọ́yẹ̀ lóri àìsàn iba àti àwọn àìsàn tó níṣe pẹ̀lú bíbí́n.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ kó di mímọ̀ wípé, oyún kejì òun ló fún òun ní ìwúrí láti ṣe àgbékalẹ̀ eré náà, àti pé eré Grey's Anatomy nípa pàtàkì lóri ṣíṣe eré náà.. | wikipedia | yo |
Eré náà gbaa àmì-ẹ̀yẹ ti eré tẹlifíṣọ̀nù tí ó dára jùlọ níbi àjọ̀dún Vues d'Afrique tó wáyé ní ìlú Montreal.Ní ọdún 2018, Aquereburu ṣe olóòtú fún ètò Les Materter d'Afrique, eré Afirika kan tí ń ṣe ìbádọ́gba ẹ̀yà eré Faransé kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ La Maison des Materter.. | wikipedia | yo |
Amal Bedjaoui (tí a bí ní 27 Oṣù Keèje, Ọdún 1963) jẹ́ olùdarí eré, agbéréjáde, àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Algeria.A bí Bedjaoui ní Algiers, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ fíìmù ṣíṣe ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga New York University.. | wikipedia | yo |
Ó pari ní ẹ̀ka Institut des Hautes Etudes Cinematoques ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga náà.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn náà, ó gba oyè gíga nínu ìmọ̀ sinimá láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga <i>Paris 1 Panther-Sorbonnei> ní ọdún 1987.. | wikipedia | yo |
Fun opolopo odun, o sise bii amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ fun didari ati iṣakoso gbigbe fiimu jade.. | wikipedia | yo |
Àkọ́kọ́ fíìmù oníṣókí rẹ̀ tí ó gbé jáde ni Une vue imprenable, ní ọdún 1993.. | wikipedia | yo |
ẹ̀kejì fíìmù oníṣókí rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ ń ṣe Shoot me an Angel jẹ́ gbígbé jáde ní ọdún 1995, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ ti Panorama níbi ayẹyẹ Berlin International Film Festival.Ní ọdún 2002, ó dá ilé-iṣẹ́ agbéréjáde kan sílẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ ń ṣe LL Productions.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún tí ó tẹ̀le, ó darí fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Un Fils, èyí tí n sọ ìtàn ọ̀dọ́mọdékùnrin kan àti ìbálòpọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú Ìyáàfin kan.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà jẹ́ títún gẹ́gẹ́ bi fíìmù tó lòdì sí àwọn òfin ìbálòpọ̀.Bedjaoui jẹ́ ọmọ olóṣèlú Mohammed Bedjaoui.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn àrùàwọn ìjáde Amal Bedjaoui ní ààyè dá fíìmù Íńtánẹ́ẹ̀tìàwọn ènìyàn ÀAlààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1963.. | wikipedia | yo |
Èkénekalicchukwu Ugochukwu Eric Nwennoi, tí alaje rẹ̀ n je Ken Erics Ugo tabi Ken Erics jẹ́ òṣèré Ori-itage, Ori Ero amo-máwòrán àti Orinrin, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó di ìlú-mọ̀ọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré sinimá kan tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ The Ilwà eré tí òṣèrébìnrin Tonto Dikeh àti Yul Edochie ti kópa.Ó sì tún jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Ángo.ìbẹ̀rẹ̀ ayé rèéon bí Eric ní Ìpínlẹ̀ Kano, ní ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù Kejì Ọdún 1985... | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ ẹta igbó ní apá ìlà oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Binta Mustapha Science ní Ìpínlẹ̀ Kano.. | wikipedia | yo |
ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama Dennis Memorial Grammar (DMgs) ní ìlú Onitsha, ní ìpínlẹ̀ Anambra Erics ti nífẹ́ sí eré ṣíṣe láti ìgbà tí ó ti wà ní kékeré.. | wikipedia | yo |
Ó lọ Zzi ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì Nnamdi Azikiwe ní ìlú Awka ní Ìpínlẹ̀ Anámbra tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ eré-oníṣe.. | wikipedia | yo |
Ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè kejì nínu ìmọ̀ eré oníṣe àti sinimá bákan náà.Iṣẹ́ ReEric bẹ̀rẹ̀ eré orí-ìtàgé ní inú ọdún 2001, níbi tí ó ti kópa nínú eré 'Holy Conwa' eré tí Chris Ubáni darí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa wẹ́wẹ́wẹ́ ní ìtara àwọn eré sinimá agbeleeo ọlọkàn-ò-íkan, láìpẹ́, ipa rẹ̀ tí ó kó nínú tí àkọ́lé ń jẹ́ Ugo, eré yí ni ó S9ó di ààyò àwọn ènìyàn nínú àwọn eré rẹ̀ tí ó kú.. | wikipedia | yo |
Èyí ni ó sì tún sí àwọn ọ̀nà àǹfàní mìíràn fún nínú agbo Nollywood.. | wikipedia | yo |
As a writer, first first published work "cell 2"o ti di ìlú-mọ̀ọ́ká, wón sì ti m loo nínú àwọn eré oríṣiríṣi àti àwọn àpilẹ̀kọ eré oníṣe gbogbo ní orí-ìtàgé àwọn àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo.. | wikipedia | yo |
Eric ma ń kọrin ní ìgbà míràn tí ó sì ma ń ta jìjí àti keyboard nínú orin rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó ti kọ àwọn orin ọlọkan-o-jọkan fún àwọn sinimá àgbéléwò pẹ̀lú.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti òṣèrékurìn tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ tí City People Entertainment Award.Ní ọdún 2017, Erille tún gba àmì-ẹ̀yẹ ti City People Entertainment Awards 2017 fún òsèrékurìn tí ó peregedé jùlọ ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ fún ti Golden Movie Awards ní ọdún 2018 gẹ́gẹ́ bi òṣèrékurìn tí ó peregedé jùlọ.Àwọn àmì-ẹ̀yẹ àkọ́ àṣàyàn eré rẹ̀ Role láá rẹ̀ lórí eré orí amo-máwòrán Playsáwọn orin Reinozi Omee (2018) You bàbá (2019) Mama (2019) LaSTERl (2019) Baby (2019) Prepersona (2019) gi n'aka (2019) Is Life (2019) Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè No Film Actors Res Setesis, Male writer Mase Actor Ọjọ́ìbí ní 1985 tún Shade àwọn Ọjọ́ìbí ní 1985.. | wikipedia | yo |
Carolé Umulinga Karemera (tí a bí ní ọdún 1975) jẹ́ òṣèré, oníjó, àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Rwanda.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ a bí Karemera ní ọdún 1975 ní ìlú Brussels.. | wikipedia | yo |