cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn kíkó ipa aṣáájú nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Manṣoo, fíìmù kan tí Ali Nuhu jẹ́ olùdarí rẹ̀.Àṣàyàn àwọn eré àko Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1997àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Diana Yẹ̀kínnì jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ọmọ orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì tó gbajúmọ̀ jùlọ fún àwọn ipa rẹ̀ nínu fíìmù bíi Ijé àti Lunchtime Heroes.. | wikipedia | yo |
Diana tún gbajúmọ̀ fún kíkó ipa Genevieve nínu eré tẹlifíṣọ̀nù Jenifa's Diary ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Fúnkẹ́ Akíndélé.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ ti “Òṣèré tí ó ní ìlérí jùlọ” níbi ayẹyẹ Golden Icons Academy Movie Awards ti ọdún 2014.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Diana Yẹ̀kínnì, ó sì dàgbà sí ìlú Lọ́ndọ̀nù, ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
O gba oye-ẹkọ lati Ile-ẹkọ giga American Academy of Dramatic Arts, eyi ti o wa ni Ilu Los Angeles, Orilẹ-ede Amẹrika.. | wikipedia | yo |
Ó ti kọ́kọ́ kọ́ ẹ̀kọ́ eré ìtàgé tẹ́lẹ̀rí ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Brit School for Performing Arts and Technology.Iṣẹ́ iṣẹ́ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 2009 nígbà tí ó fi kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù ti Amẹ́ríkà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Medium.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, ó kópa gẹ́gẹ́ bi Libby nínu fíìmù Ijé àti gẹ́gẹ́ bi Odele nínu fíìmù Mosa.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, Yẹ̀kínnì kópa tó sì jáwé olúborí nínú ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìdíje Kand screen Icon Search tí ó wáyé ní ìlú Houston, orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Annabella Zwyndila jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ káàkiri gẹ́gẹ́ bi àkọ́kọ́ Green.ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bi Annabella Zwyndila ní ìlú Ìbàdàn, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ ẹgbẹ́ ọmọ ogun ti Nàìjíríà, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ògbáṣẹ́ àgbà nídi ṣíṣe ètò ẹ̀kọ́ àwọn ará ìlú.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ìwé Command Secondary School ní ìlú Jọs, Ìpínlẹ̀ Plateau ṣááju kí ó tó lọ sí Yunifásítì ìlú Jọ níbití ó ti gba oyè ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ eré ìtàgé ṣíṣe.Àkójọ àwọn eré tí ó ti kọ́àwọ̀n ìyẹ́sí ZAFAA Awards as Best Up Actres Ìtọ́kasí àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Eve Esin jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ ti City People Entertainment Awards fún ẹ̀ka ti òṣèrébìnrin tó ní ìlérí jùlọ ní Nàìjíríà ní ọdún 2015, àmì-ẹ̀yẹ ti AMAA fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tí ó dára jùlọ àti àmì-ẹ̀yẹ AMVCA fún ti òṣèrébìnrin tó dára jùlọ nínu eré ìtàgé.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Esin ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, ní ìjọba agbègbè òròn, gúùsù Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Esin parí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní ìlú abí rẹ̀ ní Akwa Ibom.lẹ́hìn èyí, ó tẹ̀síwájú láti ka ìwé mẹ́wàá ní Immaculate Conception Secondary School tí ó wà ní agbègbè Itak-Ikọ̀, Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom níbi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí fún ìparí ẹ̀kọ́ mẹ́wàá rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Lẹhin naa, ẹsin lọ si Yunifasiti ilu Calabar ni Ipinle Cross River nibiti o ti gba oye Eko ninu imo ere itage.Iṣẹ iṣe rẹ ṣaaju ki ẹsin to darapọ mọ ile-iṣẹ fiimu ti Naijiria ti a mọ ni Nollywood ni ọdun 2008, o jẹ oṣiṣẹ ile ifowopamọ ki o to pada wa fi opin si ṣiṣẹ iṣẹ naa lati le gbajumọ iṣẹ oṣere.. | wikipedia | yo |
Esin darapo mo ile-iṣẹ fiimu ti Naijiria (Nollywood) ni odun 2008 leyin sise ayewo lati kopa ninu fiimu kan nibiti o ti ṣaṣeyọri to si je okan lara awon olukopa ninu fiimu naa.. | wikipedia | yo |
Esin ṣe àkọ́kọ́ dídarí fíìmù pẹ̀lú dídarí fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Spirit.. | wikipedia | yo |
Gẹgẹbi ile-iṣẹ oniroyin The Tribune ti ṣe sọ di mimọ, ẹsin ti ni ifihan to le ni ọgọrun-un ninu fiimu.Awon ìyẹ́sí re ni odun 2015, Esin gba ami eye City People Entertainment Awards fun ẹka ti òṣèrébìnrin tó ní ìlérí jùlọ ni Nàìjíríà. | wikipedia | yo |
Esin gba àmì ẹ̀yẹ AMAA fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tí ó dára jùlọ Esin gba àmì ẹ̀yẹ AMVCA fún òṣèrébìnrin tó dára jùlọ nínu eré ìtàgé.Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀ Blue (2019) Pains of Life (2017) Girls Are Not Srance (2017) Treasure (2017) The Storm (2016) Ṣẹ́du Who You Love (2016) OyO (2015) Idẹimi (2014) Brothers War (2013) brave Mind (2012) deep Water (2012) Hand of Fate (2012) Sins of the Past (2012) The enemy I see (2012) Gallant Babes (2011) Sunday for Coming (2011) mad Sex (2010) Royal War (2010) Oyecent ( 2005)Àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1980àwọn ọdún Àpapọ̀ àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Máyọ̀wá Nicholas tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1998 (22 May 1998) jẹ́ gbajúmọ̀ aránṣọ-ṣoge ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni aránsọ-ṣoge ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí wọ́n ṣàfihàn ní níbi ìpàtẹ oge tí Llcece & takòbana, Saint Laurent, àti Calvin Klein.Iṣẹ́dọ́gba Nicholas wà lára àwọn adíje àṣekágbá ìdíje Elite Model Look lọ́dún 2014, ó bá àwọn gbajúmọ̀ aránsọ-ṣoge orílẹ̀ èdè Italy, Greta Varlese fa kanngban nínú ìdíje náà Contest.Lọ́dún 2015, ó kọ́kọ́ kópa nínú ìpàtẹ aránsọ-ṣoge fún Bal, Calvin Klein, Kenzo, Hermes, àti ACne Studios.. | wikipedia | yo |
Láìpẹ́, ó ti bá àwọn gbajúmò aránṣọ-ṣoge bíi Prada, láàárín Fas, Veryíya, Chanel, Michael Kamirs, àti Oscar dé là Renta ṣiṣẹ́.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ náà, ó ti kópa nínu ìpàtẹ Arabíà-ṣoge ti Llcece àsèbana.Ó yẹ kó kọ́kọ́ kópa àkókò lọ́dún fún Victoria's Secret Fashion show lọ́dún 2017, ṣùgbọ́n ìjọba orílẹ̀ èdè China kọ́ fún un òun àti àwọn akópa kan ní ìwé ìrìnnà láti wọ orílẹ̀ èdè náà.. | wikipedia | yo |
O wa papa kopa ninu ninu Victoria's Secret Fashion Show lodun 2018.. | wikipedia | yo |
Máyọ̀wá ló wà lára àwọn aránsọ-ṣoge Aadọta, Models.com's "Top 50" Models to dara ju lọ ní Àgbáyé.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Chelsea Eze (tí a bí GẸ́GẸ́ bí Chelsea Ada Yeriẹ̀ri ní 15 Oṣù kọkànlá) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ pẹ̀lú kíkópa nínu àkọ́kọ́ fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Silent Scandals ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Genevieve Nnaji àti Majid Michel.. | wikipedia | yo |
Fun ipa rẹ ninu fiimu naa, o gba ami eye oṣere ti o ni ileri julọ nibi ayẹyẹ 6th Africa Movie Academy Awards .ibẹrẹ aye ati ẹkọ rẹ a bi Chelsea ni Ipinle Kano ṣugbọn o jẹ ọmọ iran ti Uahia, Ipinle Ábíá.. | wikipedia | yo |
Ó lọ ilé-ìwé Federal Government Girls College àti St.Louis Secondary School ní ìlú Kano.. | wikipedia | yo |
Ó kẹ́kọ̀ọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Yunifásítì ìlú Maiduguri.. | wikipedia | yo |
Gẹgẹbi ifọrọwanilẹnuwo rẹ kan pẹlu iwe iroyin The Punch, o wipe igba ewe oun dun gan nitoripe Ilu Kano kun fun Alaafia nigba naa.Iṣẹ iṣe rẹ ṣaaju kikopa re ninu ere Silent Scandals, o jẹ afẹwaṣiṣẹ, ko si tii ma se iṣẹ osere àyàfi awon ere ori ipele ti o se ni ile ijosin.. | wikipedia | yo |
Ṣíṣe iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ nígbà tí Vivian Ejike alásùn pèé lati wá ṣe àyẹ̀wò fún ipa amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ fún ti eré Silent Scandals.. | wikipedia | yo |
Láti ìgbà náà, ó ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù míràn bíi Two Brides and a Baby (2011), Hoodrush (2012) and Murder at Prime Suites (2013).Àkójọ àwọn eré rẹ̀àwọn ìyẹ́síàwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn òsèré ará Nàìjíríàọdún Ọjọ́ìbí Kosi (àwọn ènìyàn Alààyè).. | wikipedia | yo |
Ibinabo Fiberesima (tí a bí ní 13 Oṣù Kínní, Ọdún 1970) jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti olùṣàkóso ìdíje ẹwà tẹ́lẹ̀rí ó ti fi ìgbà kan jẹ́ Ààrẹ ẹgbẹ́ Actors Guild of Nigeria.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Ibinabo sí owó bàbá tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ìyá tí n ṣe ọmọ orílẹ̀-èdè Ireland.. | wikipedia | yo |
Ibinabo bẹ̀rẹ̀ ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ nígbàtí ó forúkọsílẹ̀ ní Y.M.C.A play Center, ní ìlú Port Harcourt ṣááju kí ó tó lọ sí Federal Government Girls College ní Ìlú New Badisa, Ìpínlẹ̀ Niger fún ètò ẹ̀kọ́ girama rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó ní òye ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, èyítí ó gbà láti Yunifásitì ìlú Ìbàdàn.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀Idije Ẹwà Ibinabo kópa nínu ìdíje ẹwà Miss Nigeria ní ọdún 1991 níbi tí ó ti ṣe ipò kejì.. | wikipedia | yo |
Ṣáájú èyí, ó ti kópa tó sì jáwé olúborí níbi ti ìdíje Miss Wonderland ní ọdún 1990, ọdún yìí kan náà ni ó tún ṣe ipò kejì níbi ìdíje Miss NUGA, èyítí ó wáyé ní Yunifásitì ìlú Calabar.Ní ọdún 1992, ó díje níbi ìdíje Most Beautiful Girl in Nigeria (MBGN) fún ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀, níbi tí ó ti ṣe ipò kèéta.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1997, ó tún díje nínú ti Miss Nigeria níbi tí ó ti ṣe ipò kejì lẹ́ẹ̀kan si ṣaájú kí wọ́n tó wá dé lánú fún ti ìdíje Miss Wonderful ní ọdún kan náà.. | wikipedia | yo |
O tun ṣe ipo kèéta fun ìdíje Most Beautiful Girl in Nigeria ẹ̀dà ti ọdún 1998.Iṣẹ osere Ibinabo kó ipa àkọ́kọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi oṣere ninu fiimu Most Wanted ki o to wá ṣe ìfihàn ninu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù Nàìjíríà míràn.Àkójọ àwọn eré rẹ̀ Most Wanted the Ghost St.. | wikipedia | yo |
Mary the Twin Sword Ladies Night the limit Letters to a stranger '76 rivers Between a Night in the Philippines Pastor's wife Camõesflage "Àwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1973àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Bikiya Graham-Douglas jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O jẹ ọmọbinrin awọn tọkọtaya oloselu Naijiria kan, Alãbò Graham-Douglas ati bọlẹ̀rẹ Elizabeth Ketebu.. | wikipedia | yo |
Graham-Douglas ti kẹ́kọ̀ọ́ ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga bíi London Academy of Music and Dramatic Art, Oxford School of Drama, Bridge Theatre Training Company àti Point Blank Music School .. | wikipedia | yo |
Ó gba oyè ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ Business Economics àti Business Law láti Yunifásítì ìlú Portsmouth, Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sìoun ni olùdásílẹ̀ bẹ́ẹ̀ta Universal Arts Foundation (BUAF).Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ ó gbajúmọ̀ fún àwọn ipa rẹ̀ nínu àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù àti sinimá àgbéléwò.. | wikipedia | yo |
Lára wọn ni flower girl, Shuga, Closer, Saro, For Coloured Girls, Suru L'ere, Lunch Time Heroes, Jenifa's Diary, Legacy àti The Battleground.Bikiya bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ nígbà tó fi kópa nínu eré ti Femi Oguns kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Torn, èyí tó wáyé ní Arcola Theatre, Ilu Lọndọnu.. | wikipedia | yo |
O ti sise pelu Africa unite Music Group, eyiti o se onígbọ̀wọ́ akoko ami-eye Best African Act nibi ayeye MoBO Awards.. | wikipedia | yo |
Ó tún ti ṣiṣẹ́ rí pẹ̀lú MTV Base Africa níbi àkọ́kọ́ ayẹyẹ MTV Africa Music Awards (Mama).àwọn ìyẹ́sí tí ó ti ní àmì ẹ̀yẹ ti Africa Magic Viewers Choice Awards (AMVCA 2014) gẹ́gẹ́ bi amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tí ó dára jùlọ fún ipa rẹ̀ nínu fíìmù flower Girl. | wikipedia | yo |
Àmì ẹ̀yẹ ti Nollywood Movies Awards (NMA 2014) Àmì ẹ̀yẹ ti Nigeria Entertainment Awards (Nea 2014) Àmì ẹ̀yẹ ti National Association of Nigerian Theatre Arts Practitioners (NANA)Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1983àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Keira Gle, (tí a bí ní 8 Oṣù kọkànlá, Ọdún 1985) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrin, àti òǹkọ̀wé, tó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ‘Keche nínu fíìmù Two Brides and a Baby, àti fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ‘Peace Nwosu’ nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Lekki Wives.. | wikipedia | yo |
aliphatic ti gba àmì ẹ̀yẹ Best of Nollywood (B) ní ọdún 2011, ó sì tún ti rí yiyan lẹẹmeji rí fún àwọn àmì ẹ̀yẹ Golden Icon Academy Awards (Kanz).. | wikipedia | yo |
.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Keira ní Ìlú Calabar, Ìpínlẹ̀ Cross River.. | wikipedia | yo |
Elizabeth lọ́kùnrin tí ń ṣe ìyá rẹ̀ jẹ́ olùkọ́ tí baba rẹ̀ sì jẹ́ ajẹ́ṣẹ́ ajíyìnrere, èyí tó mú kí ìyá rẹ̀ máa dánìkan ṣe ẹ̀tọ́ lórí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí iṣẹ́ gbé ìyá rẹ̀ lọ sí ìlú Minna ní Ìpínlẹ̀ Niger, ó mú Keira ọmọ ọdún mọ́kànlá náà dádani pẹ̀lú rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Keira àti àwọn ẹbí rẹ̀ padà kó lọ sí orílè-èdè Ghánà ní ọdún 2005, níbití ó ti forúkọsílẹ̀ ní ilé-ìwé gíga kan láti kẹ́kọ̀ọ́ ìṣàkóso Ìrìn-àjò àti Ìgbàlejò.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2006 lẹ́yìn ìparí ẹ̀kọ́ rẹ̀, Keira pinnu láti lépa ìrírí ọkàn rẹ̀ fún iṣẹ́ òṣèré ṣíṣeó lo ọdún kan sí ní orílẹ̀-èdè Ghana ní ìgbìyànjú láti ráyè lágbo eré ìdárayá ti Ghana ṣùgbọ́n Pàbó ni gbogbo rẹ̀ já sí nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ipa tí ó rí nílò sísọ èdè ilẹ̀ Ghana.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2007, ó padà sí Nàìjíríà láti tẹ̀síwájú lílépa Ireti Ọkàn rẹ̀ fún iṣẹ́ òṣèré ṣíṣe.Iṣẹ́ iṣẹ́ nígbà tí Keira bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní Nollywood, ọ̀pọ̀lọpọ̀ n ṣe àpèjúwe ìlànà ṣíṣe eré rẹ̀ láti jọ ti òṣèré akẹgbẹ́ rẹ̀ Mercy Johnson.. | wikipedia | yo |
Àkọ́kọ́ ipa Keira wáyé nínu eré tẹlifíṣọ̀nù Cross Roads tí Emeka Ossai ṣe.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, ó kó ipa aṣáájú pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Desmomd Elliot nínu fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Kajola, eré tí Níyì Akínmọlá darí.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà kọ̀ láti rí ìtẹ́wọ́gbà ní agbo eré sinimá ti Nàìjíríà.Ní ọdún 2011, ó tẹ̀síwájú láti kópa aṣáájú gẹ́gẹ́ bi 'Keche', nínú eré Two Brides and a Baby pẹ̀lú àjọṣepọ̀ OC ? Stella, Stella-Aboderin, Chelsea Eze àti Okey Uzoeshi.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré tuntun tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ ti Golden Icon Academy Awards (wùwú).Àkójọ àwọn eré àkò Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn ÀAlààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1985àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Wàyí Ahmad Idris tí a tún mọ̀ sí tàbí Idris (táa bí ní 14 Oṣù Keèje, Ọdún 1987), jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó máa n ṣiṣẹ́ lágbo òṣèré ti kannywood.. | wikipedia | yo |
Eré àkọ́kọ́ rẹ̀ tí ó ti kópa ní fíìmù Barauniya (2016).. | wikipedia | yo |
Ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dára jùlọ ní ọdún 2019.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀hìndà jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínẹ̀ Kano, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n ìlú Sagamu ní Ìpínẹ̀ Kano Ògùn ni wọ́n bí sí, níbẹ̀ náà ló sì dàgbà sí.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe àkọ́kọ́ ìfihàn rẹ̀ ní agbo òṣèré kannywood nínu fíìmù táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní Barauniya pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Ali Nuhu, àti Jamila Nagudu.Ní ọdún 2018, ó dá ilé-iṣẹ́ agbéréjáde sílẹ̀ tí ó pe orúkọ rẹ̀ ní Ramlat Investment.. | wikipedia | yo |
Adeola Deborah Olubamiji jẹ́ Onímọ̀-ẹ̀rọ ti ìlú Nàìjíríà àti Kánádà tí ó ṣe amọja ní iṣelọpọ Irin àti Ṣíṣu (tí a tún mọ ní àtẹ̀jáde-3D).Ní ọdún 2017, Adéọlá jẹ́ ènìyàn dúdú àkọ́kọ́ tí ó gba PhD nínú ìmọ̀-iṣẹ́ BioMedical láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga University ti Saskatchewan, ní ìlú Canada.Ó sì tẹ̀síwájú láti fún ọ̀rọ̀ lórí TED bí òun ṣe lo 3D títẹ́ síìta fún ìmúláradá ti iṣan Liga tí ó bàjẹ́, ní ìlú Kánádà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti Èkó rẹ̀ Adéọlá Olúbámijí ni a bí ní Oṣù kẹrin Ọjọ́ Kẹta, Ọdún 1985, àbínibí ti agbègbè ìjàrẹ̀, ìpínlẹ̀ Ondo, ní orílẹ̀ èdè Nigeria.. | wikipedia | yo |
O bẹrẹ idagba ni Ilu Ibadan nibiti o ti lọ si ile eko ni alafia ati ile-ẹkọ Secondary ni Saint Gabriel, Mokọlà.. | wikipedia | yo |
O gba oye oye ni Fisiksi (pelu ìtànná) lati ile-eko giga ti Unifasiti Olabisi OnaBanjo, lẹhinna o tẹsiwaju ti ofi gba oye BSc.. | wikipedia | yo |
Ní Tampere Unifasiti ti Technology, ní ìlú Finland.. | wikipedia | yo |
Ó gba oyè Dókítà l'àti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Unifasiti ti Saskatchewan tí ó sì jẹ́ ènìyàn dúdú àkọ́kọ́ láti gba Ph.D.. | wikipedia | yo |
Ni imo-iṣẹ BioMedical.iṣẹ rẹ o ṣiṣẹ bi oludari metallurgist ati imọ-ẹrọ ohun elo ni awọn imọ-ẹrọ Burloak lati ọdun 2016 si ọdun 2018.. | wikipedia | yo |
Lakoko ti o wa ni awọn imọ-ẹrọ Burloak, o tun ṣe bi olùbásoro alakoso fun gbogbo Lablo manufacturing Burloak's ati MultiSCale ni University of Waterloo, Ontario Canada.. | wikipedia | yo |
Lọwọlọwọ o jẹ Onimọnran Imo-ẹrọ iṣelọpọ to ti ní ìlọsíwájú ní Cummins Inc.. | wikipedia | yo |
Indiana, níbi tí a ti mọ̀ ọ́ gẹ́gẹ́bí amòye kókó-oró iṣelọpọ iṣelọpọ, ohun elo ni ìdàgbàsókè ọ̀nà opopona imọ-ẹrọ afikun, tun imudarasi láṣẹr tí Cummins ti a tẹ jáde irin alágbára irin 316l.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ ti stemhub Foundation, àbikọ́ko kan ti ìlú Kánádà tí ó fún ní agbára àti kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ, ìmọ́-ẹ̀rọ, ìmọ́-iṣẹ́ àti ìṣirò (stem) Èkó sí àwọn ọmọ ilé-ìwé àti àwọn kọ́ṣẹ́ iṣẹ́ ìbẹ̀rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní àfikún, ó joko lórí ìgbìmọ̀ ti Science Science & Innovation Inc.. | wikipedia | yo |
Oun ni alámọ̀ràn pàtàkì ní D-Tech Cenx, ilé-iṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìmọ̀-ẹ̀rọ, tí ó wà ní Ontario Canada àti Indiana ní ìlú Amẹ́ríkà.àwọn àmì-ẹ̀yẹ àti ìdánimọ̀ rẹ̀ ní ọdún 2017, amo ó bí ẹnikaàrún nínú àwọn 150 obìnrin dúdú ní ó mú kí kí Kánádà dára jùlọ, tí nṣe ìwá Ìrántí ayẹyẹ 150th ti ìlú Kánádà.ní ọdún 2019, orúkọ rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan nínú obìnrin l'Ore Paris wáwá tí ó pegede ní ìlú Canada.ní ọdún 2019, a dárúkọ rẹ̀ gẹ́gẹ́bí ọ̀kan nínú àwọn obìrin ipa ti mẹ́tàdínlógún ní iṣelọpọ Honẹ̀ ní Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Aduni Adeti ó jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, àti Modeeli ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹfà ọdún 1976.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀wọ́n bí aduni ní ìlú New York ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìlú Irish láti orílẹ̀-èdèGermany nígbà tí bàbá rẹ̀ jẹ́ Yorùbá ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tó aduni ní Ìpínlẹ̀ Èkó àti ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Èkó àti ìpínlẹ̀ Ògùn.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ fẹ́ràn ai kí ó kọ́ ìmọ̀ nípa ìṣirò owó ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì Kentucky ní ọdún 2008.Iṣẹ́ rẹ̀aduni ti ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ Madáami-Hédòfo kan ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà dáá kí ó tó dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ eré ṣíṣe.. | wikipedia | yo |
Ó dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ Modeeli tí wọ́n gbé aṣọ tuntun jáde.. | wikipedia | yo |
lẹ́yìn tí ó padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó kópa nínú eré àkọ́kọ́ rẹ̀ ní agbo Nollywood nínú eré Yorùbá kan tí wọ́n pe àkọlé rẹ̀ ní "You or i" ní ọdún 2013.. | wikipedia | yo |
O ti kúpa ninu fọ̀ràn àwo orin gbajú-gbajà olórin Sound Sultan ati ice Prince kọ́.aduni ti gba ami-ẹ̀yẹ Stella Award ní ilé-iṣẹ́ Nigerian Institute of Journalism fún ipa rẹ̀ tí ó n kó pẹ̀lú bí ó ṣe ń gbé àṣà Yoruba lárù́n.. | wikipedia | yo |
Ó di aṣojú fún ilé-iṣẹ́ Oud Maticstic ní ọdún 2017.Ìgbé ayé Readuni ti bímọ meji tí orúkọ wọn n jẹ́ D'Marion àti Ayden.. | wikipedia | yo |
Aduni fi lédè nínú ìfọ̀rọ̀wáni-lẹ́nuwò kan wípé òun kò ní fẹ́ ọkọ mìíràn mọ́ lẹ́yìn ẹni àkọ́kọ́ tí òún ti bímọ fún tí àwọn sì ti pín yà.Àwọn àṣàyàn ère rẹ̀ìwọ tàbí èmi (You or i) (2013)What's within (2014)2nd Honeymoon (2014)head Gone (2015)so in Love.. | wikipedia | yo |
She also Won Best Supporting Actress Award at the Lagos Film Festival for the Movie.The blogger's Wife (2017)gun Man (2017)boss of All Bosses (2018)The Vendor (2018)House of Contention (2019)Àwọn eré Ori amo-máwòránmáwòrán the CloudBabatunde DiariesJenifa's Diary Season 2Sons of the Calite Season 2See alsolist of Yoruba PeopleÀwọn Ìtọ́kasíàwọn Ijasomeric Film Act Actse Ènìyàn Alààyè From Queens, New Yorkamerican People of Nigerian descentacan People of Yorùbá descenmérì EmiGrants To Nidelectct in Yoruba Cin21st-Century Nigerian Actresses, Television Actresses Actresses Act, People of German descencan People of German descenàpótí of Kentucky Aluhan Ọjọ́ìbí ni 1976actresses from Lago Bal's Next Model League Ikejisa Female Models Femalels Fromlslsls From New York City City Mo Models of Birth Missing (Living People) of German Descent.. | wikipedia | yo |
Demi Isaac Oviawe (tí a bí ní 2 Oṣù Kọkànlá, Ọdún 2000) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní orílẹ̀-èdè Ireland.. | wikipedia | yo |
O gbajumọ fun ipa rẹ gẹgẹ bi Linda Walsh ninu eré The Young Offenders ti ọdun 2018.Oviawe dagba ni ilu Mallow, Orilẹ-ede Ireland si ọwọ awon obi rẹ.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí Oviawe dìídì sọ lórúkọ tó ṣe gẹ́gẹ́ ti òṣèrébìnrin Demi Moore.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí Oviawe wà ní ilé-ẹ̀kọ́ girama, ó kópa nínu ṣíṣe àwọn eré ìdárayá bíi Camvgíẹ́ àti Gaelic football, ó sì tún kópa nínu àwọn ìbádọ́gba eré ìtàgé ti ilé-ìwé fún àwọn eré bíi Beauty and the Beast, Grease àti Sister Act.ní ìbẹ̀rẹ̀, Oviawe n gbèrò láti ṣiṣẹ́ olùkọ́ ilé-ìwé ṣùgbọ́n ní ọdún 2017, ó kópa nínu àyẹ̀wò kan lóri YouTube fún ti eré tẹlifíṣọ̀nù The Young Offenders, ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n yàn fún eré náà láti kó ipa Linda Walsh.Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀ tẹlifíṣọ̀nù Ìtọ́kasíàwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 2000àwọn ènìyàn Oṣù ará ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oghenekaro Lydia Itene jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti olùṣòwò.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ Oghenekaro Itene wá láti Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, ṣùgbọ́n wọ́n bí ní ìlú Benin, Ìpínlẹ̀ Ẹdó níbi tí ó dàgbà sí.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ akẹ́kọ-gboyè láti ilé-ìwé gíga Yunifásítì ìlú Benin.. | wikipedia | yo |
Àkọ́kọ́ ṣíṣe eré ìtàgé rẹ̀ wáyé nígbàtí ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ eré ìtàgé ní ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ́mọ ọdún mẹ́jọ.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ Itene ṣe ìfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òṣèré ní ọdún 2013 nínu fíìmù Shattered Mirror, èyí tí olùdarí rẹ̀ n ṣe Lancelot Imasuen Oduwa.. | wikipedia | yo |
Ó kópa gẹ̀gẹ̀ bi Simi nínú eré kan tí ilé-iṣẹ́ Total Recall ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó sinmi ṣíṣe fíìmù fún bi ọdún kan ṣaájú kí ó tó wá padà ní ọdún 2015 nígbà tí ó fi kópa nínu eré MNET Africa kan táa pè ní Tinsel.. | wikipedia | yo |
Ó tún hàn gẹ́gẹ́ bi Sonia nínu fíìmù Glass House, èyí tí Africa Magic ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀ ní ọdún 2016.Àṣàyàn àwọn eré àkò fíìmù Shattered Mirror (2014) Born Again Sisters (2015) The Prodigal(2015) Glass House (2015) Esohe (2017) Away From Home(2016) The Quest (2015) Chase (2019 film)àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù Tinsel Lincoln Odu The Sanọ̀wọ́àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn tíàwọn òṣèré ará Nàìjíríà Ọjọ́ìbí Ọjọ́ìbí (àwọn ènìyàn Alààyè Al).. | wikipedia | yo |
Carol King (tí a bí ní 24 Oṣù Keèje, Ọdún 1963) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa rẹ̀ bi “Jùmọ̀kẹ́” nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Everyday People.. | wikipedia | yo |
Carol jẹ́ ẹnìkan tí ó máa ń sábà kó ipa ìyá lọ́pọ̀lọpọ̀ nínu àwọn eré, ó sì ti ṣe bẹ́ẹ̀ hàn nínu àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù àti sinimá àgbéléwò bíi The Gods Are Still Not To Blame àti Dazzling Mirage ti Tunde Kelani.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Carol ní ìlú Èkó, sí ọwọ́ àwọn òbí tí wọ́n wá láti Ìpínlẹ̀ Ẹdó.. | wikipedia | yo |
Sòwẹ́tò Primary School àti Awori Anglican Comprehensive High School ní ìlú Èkó, fún ètò ẹ̀kọ́ alákọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama rẹ̀.. | wikipedia | yo |