cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
O kawe ni ibeere aye rẹ ni fountain Nursery and Primary School, ati Nigeria Navy Secondary School, gbogbo rẹ ni Ipinle Eko ki o to tẹ siwaju ninu ẹkọ rẹ ni University of Lagos, nibi ti o ti kawe gboye ninu imọ ofin (Law) .. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2000, ó pegedé, wọ́n sìn pé ẹ sí Nigerian Law school ní Abuja.Iṣẹ́ Tít Fúnkẹ́ ṣíṣe amòfin fún ìgbà díẹ̀, ilé-iṣẹ́ agbódegbà ìpolówó-ọjà, tiẹ̀ Communications gbà á, ó sin ṣíṣẹ́ níbẹ̀ fún ìgbà díẹ̀.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó di ọdún 2003,ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ olùṣètò ètò, ó sin dá ilé-iṣẹ́ Zapphaire Events sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Láti ìgbà náà, ó bá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn àti ilé-iṣẹ́ ṣètò àwọn ètò ayẹyẹ wọn ní Nàìjíríà àti nílókè okùn.. | wikipedia | yo |
Lórí iṣẹ́ yìí, ó ti gba àìmọye Àmin-ẹ̀yẹ, débi pé ilé-iṣẹ́ oníròyìn òkè òkun, CNN ṣe àfihàn rẹ̀ nínú ètò wọn kan tí wọ́n pè ní Inside Africa .. | wikipedia | yo |
Lara awon amin-eye ti o ti gba ni "onisowo to pegede julo lodun 2006" amin-eye fun abániseto to dara ju lo lo lodun re.Àwọn ìwé rẹThe Masẹntial Britola Handskáwọn gbajúmọ̀ 2014, ìkànnì onílogun Naijiria kan, YNaija kan mo maa awon gbajumo omo Naijiria omo Naijiria ti ojo ori ori ko ju ogoji lo.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ náà lọ́dún 2016, BBC dárúkọ rẹ̀ mọ ọgọ́rùn-ún gbajúmọ̀ obìnrin tí wọ́n mọ̀ ní àgbáyé.Ìgbésí ayé ara rẹ̀Funke Bucknor-Obruthe fẹ́ Onome Obruthe, wọ́n sìn bímọ méjì fún ara wọn.. | wikipedia | yo |
Òun ni ẹ̀gbọ́n fún gbájúmọ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́, Tosyn Bucknor.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Georgina onoha jẹ́ òṣèré Nollywood, afẹwàṣiṣẹ́, olóòtú ètò tẹlifíṣọ̀nù àti afowokòpọ̀.. | wikipedia | yo |
Ó wá láti ìpínlẹ̀ Anambra ni gúúsù ìlà-oòrùn Nàìjíríà... | wikipedia | yo |
O darapọ mọ iṣẹ fiimu ti Naijiria ni ọdun 1990 nigba to wa lọ́mọ ọdun mẹ́wàá.. | wikipedia | yo |
Ṣùgbọ́n ó di gbajúmọ̀ ní ọdún 1992 lẹ́hìn kíkópa rẹ̀ nínú ère “Living in Bondage.” Wọ́n yàán fún òṣèré amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tó dára jùlọ níbi ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó fẹ̀hónú rẹ̀ hàn gbangba gbangba lórí ìgbésẹ̀ ìjọba Nàìjíríà láti fi owó kún owó epo ètùtù.“ | wikipedia | yo |
Ninu ifiweranṣẹ InstagRamu re ni osu kèéta odun 2016, o je ko di mimo wipe oun ti n ba aisan kan FAa lati bi odun mejo sẹ́yìn.Awon itọkasi awon eniyan Alààyèawon osere ara Naijiriaodun Ọjọ́ìbí Kosi (awon eniyan Alààyè).. | wikipedia | yo |
Reanne Weruche Opia (tí a bí ní 11 Oṣù Kẹẹ̀rin, Ọdún 1987 ní Nàìjíríà) jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè Btìwá, ó sì tún jẹ́ olùṣòwò.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ aláàkóso ilé ìtajà rẹ̀ tí ó dá sílẹ̀ táa pe orúkọ rẹ̀ ní Jesus Junkie Clovi. rẹ̀ Weruche gbajúmọ̀ fún kíkó ipa Cleopatra Ọfọ̀ nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Bad Education.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, wọ́n yan Weruche fún àmì ẹ̀yẹ "Nollywood Actress of the Year" níbi ayẹyẹ 2015 Nigeria Entertainment Awards.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2018, Opia dì jọ kópa pẹ̀lú Steve Pemberton àti rèéce Shearmith nínu ìpele ẹ̀kẹfà àti ìkẹhìn ti eré "Temté Fate." Opia tún ti kópa nínu eré BBC kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ì May Destroy You, èyítí ó kọ́kọ́ jẹ́ gbígbé sáfẹ́fẹ́ ní Oṣù Kefà ọdún 2020.. | wikipedia | yo |
Opia ti ní oyè-ẹ̀kọ́ nínu eré ìtàgé àti ìmọ̀ àwùjọ.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ ògbógbó agbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti olùgbàlejò lóri ètò tẹlifíṣọ̀nù Ruth Benamaisia Opia.àwọn àṣàyàn eré àkò ìyẹ́sí ní Ìtọ́kasí àwọn onísí ara Nàìjíríà. ènìyàn ÀAlààyèàwọn òṣèré Ara Naiàwòrán Ọjọ́ìbí ní 1987.. | wikipedia | yo |
Cossy Orjiakor (tí a bí ní 16 Oṣù Kẹẹ̀wá) jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, olùgbéréjáde, akọrin, àti oníjó.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ lẹ́hìn tí ó hàn nínu fidio orin kan tí Obesere ṣe.. | wikipedia | yo |
Àwọn Gibeah sì tún wà lórí pé ó máa ń fi ọmú rẹ̀ hàn síta tí ó bá wà láàrín àwùjọ àti nígbà tí ó bá ń ṣiṣẹ́ ìjọ rẹ̀ nínú fídíò orin.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, ó ṣe àkọ́kọ́ àgbéjáde fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Power Girls, láti ilé-iṣẹ́ rẹ̀ táa pè ní Playgirl Pictures.ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ a bí Orjiakor ní Ìpínlẹ̀ Anámbra.. | wikipedia | yo |
ó parí ilé-ìwé gíga pẹ̀lú gbígba oyè nínú ìmọ̀ ìṣirò àti ìṣàkóso láti Yunifásítì ilẹ̀ Nàìjíríà ti ìlú Nsukka, ó sì padà tún gba oyè gíga láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ìpínlẹ̀ Èkó.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ Orjiakor jẹ́ ẹni tí àwọn èyàn mọ̀ fún fífi ọmú rẹ̀ hàn síta láàrin àwùjọ.. | wikipedia | yo |
O ṣe apejuwe ọmú rẹ gege bi ọrẹ nla lati ọdọ Ọlọrun, o si sọ di mimọ wipe oun ki yoo fun awọn ọmọ oun lọmú bi Alára.. | wikipedia | yo |
Awuyewuye sì tún wà lórí pé ṣíṣí igbá àyà rẹ̀ síta lẹ́kún n tó fi tètè di ìlúmọ̀ọ́ká.. | wikipedia | yo |
Ìwé ìròyìn Daily Post àti Vanguard ṣe apejuwe rẹ bi oṣere onirawọ ọmú ti Nollywood.. | wikipedia | yo |
Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan pẹ̀lú ìwé ìròyìn encomium, ó ṣàlàyé wípé ṣíṣe ìyá àwọn ọmọ òun mú lémi òun ju níní ọkọ lọ.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ Orjiakor ti ṣiṣẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ oríṣiríṣi eré ìdárayá.. | wikipedia | yo |
O ti ṣe ifihan ninu awọn fidio orin ati fiimu, o si ti kọ ọpọlọpọ orin.O ṣe agbejade akoko akojopo awọn orin rẹ ti akọle rẹ jẹ Nutty Queen ni ọdun 2013, eyiti o ṣalaye wipe o ni ọpọlọpọ ẹkọ pataki ninu.. | wikipedia | yo |
O so di mimo wipe oun ko dédé maa si ara oun sile lasan bi ko se pe lati maa fi se ipolowo ara re ni agbo ere idaraya.Awon aṣayan ere rẹ Itohan (didari latọwọ Chico Ejiro ) ara Saraphina Anini amobi Milionu kan ọmọkunrin Papa Ajaawon itọkasi awon eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1984awon osere ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Olùwà Bucknor ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sí tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún Oṣù Kẹjọ Ọdún 1981,ó sin ta tẹrú nípàá lọ́jọ́ kọkàndínlógún Oṣù Kọkànlá Ọdún 2018 (15 August 1981 - 19 November 2018), jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́, òṣèrébìnrin àti gbajúmọ̀ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ lórí Ìtàkùn abanidọ́rẹ̀ẹ́ Ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àyè rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí Tosyn sí ìdílé gbájúmọ́ olórin, ọ̀gbẹ́ni Segun Bucknor àti Ìyáàfin Sola Bucknor.. | wikipedia | yo |
Inú oko ni wọ́n bí i sí lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹjọ ọdún 1981.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ni gbajugbaja abaṣeto eto, Funke Bucknor-Obruthe, Alase ati Oludasilẹ Zphaphaire Events.. | wikipedia | yo |
Tosyn kawe ni fountain Nursery and Primary School, Queens' College, Yaba, University of Lagos (LLB) ati The Nigerian Law School, ni Ipinle Eko.. | wikipedia | yo |
O sin ile baba rẹ, National Youth Service Corps ní Port Harcourt, nibi ti o ti ko awọn akekoo ni Litireso ede oyinbo ati ede oyinbo ni Archdeacon Crowther Memorial Girls' School, Elelenwo.Iṣẹ o bẹrẹ iṣẹ redio pẹlu tẹ̀ẹ́-a lori ikanni Eko 89.7FMFM, leyin eyi, o sise-kose (Internship) ni Cool 96.9FM nibi ti o ti se atọkun eto fun Hour Show on Saturdays.. | wikipedia | yo |
Nígbà ìfilú rẹ̀ lọ́dún 2009, Tosyn ní atọ́kùn ètò àárọ̀ lórí ìkànnì rédíò 90.9FM.. | wikipedia | yo |
Awo orin kan pere Pop Rock Soul and jara ló gbé jáde.. | wikipedia | yo |
Bó nínú àwọn orin rẹ̀ ni wọ́n lò fún sinimá àgbéléwò kúkurú ìrètí.. | wikipedia | yo |
Ó kọrin, kọ̀wé orin àti ṣe Akale orin gege bi con.tra.diction.Tosyn ti ba awon gbajumo olorin bii Skales, Rooftop Mcs àti Eva, ↑ Tintin, Coldflaflames, DJ Klem, Knighìrẹ́pọ̀, Migbuxx ati Cobhams sise.Tẹlifíṣọ̀n Tosyn ti se atọ́kùn ètò ti o pe ni Tosyns Buzz LIVE lórí ìkànnì Pulse TV ni gbogbo ọjọ Ẹtì.. | wikipedia | yo |
2012 Judge on Greensprings PAStoral Centre Talent Show (C's Got Talent), Greensprings School, Lekki.. | wikipedia | yo |
kópa nínú orin Miominx Music E-Mix Mixìtura pẹ̀lú Darey, àṣà, Goldie àti àwọn mìíràn.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Mercy Chinwo jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, akọrin àjíajíyìnrere àti akọ̀wé orin ọmọ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun lo gbamin ẹyẹ ìdíje Nigerian idol abala keji ti ọdun 2012.igbesi aye ati ise rẹwọn bi Mercy Nnenda Chinwo lọjọ karun-un osu Keta-an ọdun 1990 ni Port Harcourt, Ipinle Rivers.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin lọ́mọdé, gẹ́gẹ́ bi ẹgbẹ́ akọrin níṣe ìjọ́sìn wọn.Mercy Chinwo gbé orin rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde lọ́dún 2015,tí ó pè ní "Àgbémọ́ny", lẹ́yìn náà, ó gbé orin mìíràn tí ó pè ní "Igwe" jáde lọ́dún tó tẹ́lẹ̀.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2019, gba Àmín-ẹ̀yẹ mẹ́ta gẹ́gẹ́ bí olórin ajíyìnrere tó dára jù, olórin obìnrin tó dára jù lọ́dún náà àti orin rẹ̀, Exré Love gẹ́gẹ́ bí orin tó dára jù lọ́dún náà níbi ìdíje àkọ́kọ́ Africa Gospel Awards Festival (àga 2019).Apapo Iṣẹ orin Reru on Orin The Cross My gaze (2018) nátì (2020)orin Adagbéjáde Tẹsnis (2015:2015) (2016)Exbu Love (2018) OyO (2018)No More Pain (2018) Chinedum (2018)Power belongs to Jesus (2019) Puce (2019) Jesús! (2019) (2019) Pil (2020) of Your Power (2020)na You Rísan FM(2020) àgbéléwòàwọn Ìtọ́kasí | wikipedia | yo |
Cynthia Shalom (tí a bí ní 18 Oṣù Kẹẹ̀ta, Ọdún 1988) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, agbéréjáde àti olùṣòwò.. | wikipedia | yo |
O jẹ ajawe olubori nibi abala Kọkànlá ti eto, Next Movie Star.lati igba naa lo ti wa kopa ninu ọpọlọpọ awọn fiimu Nollywood.. | wikipedia | yo |
Ó kópa nínu eré alátìgbà-dègbà tí M-Net kan tí àkọ́lé rẹ̀ Jẹ́Tinsel.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Cynthia Shalom ní ìlú Éyìn, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.. | wikipedia | yo |
Ó lọ ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama rẹ̀ ní Port Harcourt níbi tí òun àti àwọn òbí rẹ̀ dì jọ ń gbé.. | wikipedia | yo |
O gba oye-ẹkọ ninu imọ iṣakoso lati ile-iwe giga Yunifasiti Ilu Port Harcourt.. | wikipedia | yo |
O si tun gba iwe eri fun ere sise nibi ajọdun Africa International Film Festival (AFRI).. | wikipedia | yo |
Ninu ifọrọwanilẹnuwo kan pẹlu awọn oniroyin Vanguard Nigeria, o sọ di mimọ wipe kikọ lo oun si Ilu Eko jẹ lati lepa iṣẹ ere itage rẹ ni ṣiṣe.Iṣẹ iṣẹ rẹ Shalom jẹ Ajawe olubori nibi eto, Next Movie Star ti ọdun 2015/2016.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe àkọ́kọ́ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òṣèré nínu ètò tímọ́naLisa dilẹ̀ kan tí àkọ́lé rẹ̀ JeYou&i With Monalisa.. | wikipedia | yo |
O wi fun iwe iroyin The Punch pe oun koju awọn ìjákulẹ̀ lọpọlọpọ nigba ti oun fẹ bẹrẹ si ni ṣe ere Nollywood.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó kó àkọ́kọ́ ipa sinimá àgbéléwò rẹ̀ nínu eré an Hour with The Shreve pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Annie Macaulay-Idibia, Gbegbe Ajibade, àti Segun Arinze.. | wikipedia | yo |
Ó tún dì jọ kópa pẹ̀lú Desmond Elliot nínú eré The Damned tí ÌrókòTV ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
ní ọdún 2018, Shalom náà dá ilé-iṣẹ́ tó n risi gbígbé eré jáde sílẹ̀, èyítí ó pe orúkọ rẹ̀ ní Cynthia Shalom Production.. | wikipedia | yo |
Ipa rẹ̀ tó kó nínu ọ̀kan lára àwọn fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Chain, ṣokùn fa yíyan rẹ̀ fún àwọn àmì ẹ̀yẹ méjì kan níbi ayẹyẹ 2019 Best of Nollywood Awards.Àwọn àṣàyàn eré Wbaa eré àgbéléwò Next Movie Star (2015/2016) Iquo's Journal (2015).[14] An Hour With The ShẸwà (2016) Rhi of Love (2016) No I Dont (2017) The Damned (2017) Roberta (2017) Karma (2017) Ẹbọ (IrokoTV) (2018).[15] Chain (2018) Driver ( 2018) Altered lati (Africa Magic) (2019) Beauty in the 2016 (Iroko (Iroko) (2019) The Second Ara 2020). | wikipedia | yo |
Back to the Wild (ÌrókòTV) (2019) Love Castle (2019) Rachel's Triumph (2019) shut (2020) FAding Blues (IrokoTV) (2020) Wind of desire (2020) Birth hurts (2020)eré Telifisonu Dear Diary Season 2 (2016). | wikipedia | yo |
Tales of Eve (2017) IIyawove (2019) Jela (2019) Tinsel (2017-present)Àwọn Ìtọ́kasí Àwọn Ènìyàn AlààyèÀwọn Ọjọ́ìbí ní 1988Àwọn Òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ada Ògochukwu Ehi tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlógún Oṣù Kesàn-án Ọdún 1987 (18 September 1987), simply known by Her Stage Name jẹ́ akọrin ajíyìnrere, onkọ̀wé orin àti òṣèrébìnrin ọmọ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó wà lọ́mọdún mẹ́wàá ló ti bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ nígbà tí ó gbé orin fún akọrin ọmọdé ẹgbẹ́ rẹ̀, Tosin Jẹ́gẹ́dẹ́.. | wikipedia | yo |
Láti ìgbà tí ó ti ń kọrin lábẹ ilé orin, LoveWorld Records lọ́dún 2009, ló ti di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká olórin.Ìgbésí ayé rẹ̀ìgbésí ayé rẹ̀ àti àti ìgbéyàwó wọn bi àdá sí ìdílé Victor àti Mabel Nduka, òun, òun àti àwọn àbúrò rẹ̀ mẹ́ta dàgbà sí ìdílé Ìgbàgbọ́ pẹ̀lú Gbígbọ́ orin Ìgbàgbọ́ Ìgbàgbọ́.. | wikipedia | yo |
Nígbà tó wà lọ́mọ ọdún mẹ́wàá, wọ́n yàn án pọ̀ mọ́ àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin tí ó wà nínú ìkọ́ àgbérìn fún gbajúmọ̀ ọmọdé olórin TÓSÌN jẹ́gẹ́dẹ́.. | wikipedia | yo |
Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ olóró * (Chemi & Polymer Engineering) ní Lagos State University, ní àkókò náà, ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ ììsìn tàbí Taiwan Love Campus Fellowship.leyin náà, ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ akorin Christy Embassy, tí ó sìn darapọ̀ mọ́ LoveWorld Records dún 2009.Ó pade ọkọ rẹ̀, Moses Ehi, ní ijo Christ Embassy Church nínú ẹgbẹ́ akorin.. | wikipedia | yo |
Wọ́n fẹ́ ara wọn lọ́dún 2008,wọ́n sìn bímọ méjì fún ara wọn.Iṣẹ́ orinláti ìgbà tí ó ti dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ akọrin Ìjọ Christ Embassy, ó ti bá wọn kópa nínú oríṣiríṣi ètò káàkiri Nàìjíríà àti ní àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé .. | wikipedia | yo |
Àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́ tí ó pè ní Unirọ́torí ló gbé jáde lọ́dún 2009, tí ó sìn gbé ìkejì jáde lọ́dún 2013 èyí tí ó pè ní lifted & So fly.. | wikipedia | yo |
Awo orin re koko ti o pe ni Future now, jade lodun 2017, o sin di orin gbajumo akoko ni ikanni Sees Nigeria yoko to jade gangan.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Abimbola Craig (ti a bi ni ọjọ keta ọjọ Kọkànlá oṣu 1986) jẹ oṣere Nollywood ti Naijiria ti o ṣe irawọ bi Tiwalade ni arabinrin arabinrin ni Transit .. | wikipedia | yo |
Lakoko o jẹ lati jẹ olupilẹṣẹ ti girl skiny ni Transit ṣugbọn o pari ni jijẹ Olóri.. | wikipedia | yo |
Láti àkókò 1, Abimbola ti lọ siwaju lati kii ṣe iṣẹ́ nikan ṣùgbọ́n ó tún ti ṣe àkọ́kọ́ 2 - àkọ́kọ́ 6 ti Sgit.. | wikipedia | yo |
Craig bákannáà ṣe àgbéjáde fíìmù ọfiisi ọfiisi “Sugar Rush” ní ọdún 2019, pẹ̀lú Jádesola Osiberu.</>Iṣẹ Iṣẹ Craig n ṣiṣẹ lọwọlọwọ bi ori ti iṣelọpọ ní Ndani àwọn ibaraẹnisọrọ, eyiti a tun mọ ni Ndani TV n ṣe àwọn ifihan pẹlu ọmọbìnrin Skinny ní Transit, awọn ipele, ruMor has it ati oje etc.Àwọn ọna asopọ Ita Abimbola Craig on Instagram Abimbola Craig on imdbáwọn ẹ̀nìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ni 1986.. | wikipedia | yo |
Barbara Soky (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ Bara Sokoko ) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti akọrin tẹ́lẹ̀rí tí ó di gbajúmọ̀ lẹ́hìn kíkópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Mirror in the Sun.. | wikipedia | yo |
Ó sinmi iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ lẹ́hìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ipa ní àwọn ọdún 80 àti 90, kí ó tó padà sí ní bá iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ lọ nísẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó ti wá ṣe bẹ́ẹ̀ hàn nínu àwọn sinimá àgbéléwò Nollywood àti àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù.Iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ àkọ́kọ́ ipa gboogi tí Soky kó wáyé nínu eré tẹlifíṣọ̀nù Inside Out èyí tó jẹ́ gbígbé sáfẹ́fẹ́ lóri ìkànnì NTA.. | wikipedia | yo |
Soky tún ti kópa pẹ̀lú Adiela Onyedibia nínu eré You Can't Take Your Wife to New York, eré kan tó dá lóri aṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tó fẹ́ ìyàwó aláìkàwé kan.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ti ere Inside Out pari, Soky gbéra láti Ìpínlẹ̀ Rivers LỌ sí ìlú Èkó níbití ó ti padà wá kópa nínu eré Mirror in the Sun ti lọlá Fani-Kayode se.. | wikipedia | yo |
Ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré kan gẹ́gẹ́ bi Yinka wọlé ṣokùn fa kíkan òkìkí rẹ̀ tó sì di ìlúmọ̀ọ́ká, débi pé ó padà wá ṣe ìpolówó ọjà fún ilé-iṣẹ́ Jik.. | wikipedia | yo |
Soky jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùkópa àkọ́kọ́ ti eré Ripples láti ọdún 1988 sí 1993.Lẹ́hìn ìsinmi ọlọ́dún mẹ́tàlá rẹ̀ nídi iṣẹ́ òṣèré, Soky padá sí ìdi iṣẹ́ òṣèré pẹ̀lú kíkópa nínu eré Amaka Igwe kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Solitaireire gẹ́gẹ́ bi Nkoyo Broderick, obìrin kan tó pinnu láti dáàbò bo ọ̀rọ̀ ẹbí rẹ̀.Iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀ ní ọdún 1986, Soky ṣe àgbéjáde àkójọpọ̀ àwọn orin rẹ̀ tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Going Places láti ilé iṣẹ́ Mercury Records.Àwọn ìyẹ́sí rẹ̀ ní ọdún 2013 Soky gba àmì ẹ̀yẹ ti òṣèré amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ 2013 Nollywood Movies Awards fún iṣẹ́ takuntakun rẹ̀ nínu fíìmù Bridge of Hope.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014 ó tún rí yíyàn fún àmì ẹ̀yẹ yìí kan náà níbi ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards fún ti ipa rẹ̀ nínu fíìmù Brothers Keeper.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ Soky bí ọmọbìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Maxine.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn òsèré ará Nàìjíríàọdún Ọjọ́ìbí Kosi (àwọn ènìyàn Alààyè).. | wikipedia | yo |
Maureen Solomon (tí a bí ní 23 Oṣù kejìlá, Ọdún 1983) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tí ó ti kópa nínu àwọn eré ti Nàìjíríà tó ti lé ní ọgọrin làkókò ìgbà tó fi ń ṣiṣẹ́ òṣèré lọ́wọ́.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ á bí Solomon ní ìlú Isuochi, Ìpínlẹ̀ Ábíá, níbi tí ó ti ka ìwé mẹ́fà àti ìwé mẹ́wàá rẹ̀ ní ilé-ìwé Isuochi Primary and Secondary School ti Ìpínlẹ̀ Abiakpínlẹ̀ Ááá . Iṣẹ́ rẹ̀ Solomon ṣàlàyé nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan pé òun bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní orí ìpele làkókò ìgbà tí òún wà ní ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Láti ìgbà náà sì lòlònì ti máa ń gbàá lérò láti fi iṣẹ́ òṣèré náà ṣiṣẹ́-jẹun lọ́jọwájú.. | wikipedia | yo |
Solomon kó ipa àkọ́kọ́ rẹ̀ nínu sinimá ti Nàìjíríà nígbà tó wà lọ́mọ ọdún mẹ́tàdínlógún níbi eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Alternative tí olùdarí rẹ̀ sì jẹ́ Lancelot Oduwa Imasuen.. | wikipedia | yo |
Solomon ṣàpèjúwe àkọ́kọ́ àyẹ̀wò rẹ̀ fún fíìmù Alternative gẹ́gẹ́ bi nkan tó wáyé látara àṣìṣe Lancelot Oduwa Imasuen tí ó síì mú fún ọ̀kan nínu àwọn tí wọ́n forúkọsílẹ̀ fún àyẹ̀wò náà.. | wikipedia | yo |
O sọ di mimo wipe n2000 ni won san fun oun fun ipa ti oun pada ko ninu ere naa ni ọdun 2001.. | wikipedia | yo |
Solomon dáwọ́ ṣíṣe fíìmù ti Nàìjíríà dúró ní ọdún 2011.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ Solomon ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú Ọ̀gbẹ́ni Okereke, Ọkunrin Dókítà Ìṣẹ́gun kan, wọ́n sí ti jọ bí àwọn ọmọ méjì.Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ lá heart of Stone (2010) Kiss The dust (2008) Angel of My Life (2007) Dd Soul (2007) Final War (2007) Help Me Out (2007) Men on Hard Way (2007) Total War (2007) Leap of Faith (2006) The Lost Son (2006) The snake Girl (2006) Oroko Lives Again (2006) Without Apology (2006) Baby Girl (2005) Blood Battle (2005) C.I.D.D (2005) Desperate Love (2005) Diamond Forever (2005) Forness (2005) Love is a Game (2005) Home Apart (2005) Ṣẹ́du me (2005) My School Mother (2005) Red Light (2005) Rising Moon (2005) Songs) Sorrow (2005) Suicide Lo Lo (2005) Test of Man (2005) Expensive Game (2005) C (2005)Àwọn Ìtọ́kasí ( Ọjọ́ìbí ni 1983 ni 1983 Gbogbo Kingdom ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Dolly Unachukwu (tí a bí ní 1 kọkànlá Oṣù 1969) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, agbéréjáde, ònkọ̀wé, àti olùdarí.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ káká orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bi Fabe Akin-Thomas nínu eré tẹlifíṣọ̀nù Fortunes.A bí Dolly Unachukwu ní ọdún 1969 sí ìdílé eleyan méje kan.. | wikipedia | yo |
Unachukwu bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré nígbà tó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rìndínlógún.. | wikipedia | yo |
O jẹ ọmọ bibi Ilu amichi ni Ipinle Anambra.akoko ifihan rẹ ninu ere waye ni ọdun 1985 nibi ti o ti kopa gẹgẹ bi Akowe.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ìgbà náà ló kópa nínu eré Mirror in the Sun gẹ́gẹ́ bi Prisca.Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀ Mirror Mirror in the Sun (TV) 1986 Fortunes (TV) 1993 Deadly Affair 1995 1&2 1994 Glamour 2 1995 Tears Tears for Love 1996 City Affair II 1997 Deadly Passion 1997 Wilst Dream 1997 Love Without language 1998 Fidu of Pontifical 1998 Father Moses 1999 Fuls Moon 1 & 2 1999 of Roses 2000 The Empire 2005 Sisters Love Love _ Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè Ọjọ́ìbí ní 1969 ní òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Tí wọ́n bí lọ́dún 1980 jẹ́ gbajúmọ̀ lọ́pọ̀ obìnrin olórin ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.Ìgbésí ayé rẹ̀ àti iṣẹ́ orin rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ lọ́dún 1986 ló gbé àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde tí ó pè ní Children Arise.. | wikipedia | yo |
O kawe gboye ninu imo Business decision and Analysis lati University of Bristol, ni London, o sise fun igba die ni United Kingdom ki o to pada si Naijiria lodun 2008.Iya Tosin ku lodun 2012.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn náà, ó dá ilé iṣẹ́ àfọwọ́ṣàánú sílẹ̀ tí ó pè ní One Book One Child, Ó ń fi èyí ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọdé Nàìjíríà.Àṣàyàn àwo àwo orin rẹ̀Children Arise (1985)kùn of Africa (1989)Children of Africa (1992)àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Maryam Yahaya jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó máa n ṣe àwọn eré kannywood.. | wikipedia | yo |
O gbajumọ fun kikopa re ninu fiimu Taraddadi, ti elnass Ajenda jẹ oludari.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yan Maryam Yahaya gẹ́gẹ́ bi òṣèré tí yóó gòkè àgbà lọ́jọwájú níbi ayẹyẹ City People Entertainment Awards ní ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
O tun ri yiyan lẹẹkan si fun ami ẹyẹ ti oṣere ti o dara julọ nibi ayẹyẹ City People Entertainment Awards ti ọdun 2018.Iṣẹ iṣẹ rẹ Yahaya ti ni ipinnu lati igba ewe rẹ lati ṣiṣẹ oṣere, nipasẹ awọn ere kannywood ti o ti maa n wo nigba to wa lọmọdé.. | wikipedia | yo |
O ṣe akọkọ ipa rẹ ninu fiimu ti akole rẹ jẹ Gidan abinci, ṣaaju awọn fiimu miran bi Barauniya ati tabo nibi ti o ti ko awọn ipa kékèèké.. | wikipedia | yo |