cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
O jẹ Alaga, eeka ti awon imo-eko BiAllah, koleeji ti imo oogun, Yunifasiti ilu Roosevelt lati odun 2010 si odun 2017..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2004 títí di àkókò yí ní Moji Adeyeye ti jẹ́ alákòóso ti àwọn oogun fún àrùn Komi AIDS ati awon alaisan HIV (DAH) eyi ni Igbimọ tí ó n pinnu láti dènà HIV/àrùn Komi AIDS ní àárín àwọn Ọ̀DỌ́ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Dídènà kí àrùn yí ma ba a ran láti ọ̀dọ ìyá sí ọmọ àti abojuto àwọn ọmọ alainibaba àti àwọn ọmọde ní ìpínlẹ̀ Èkó Èkó, Ìpínlẹ̀ Osun àti ìpínlẹ̀ Oyo ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O jẹ alákòóso awon oogun fun arun kogboogun AIDS ati awon alaisan HIV (DAH), ori ipo yi ni o wa lati odun 2004..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2004 sí ọdún 2005, ó jẹ́ olùkọ́ àgbà ti Fulbright, éékà tí Èkó ìmọ̀ Oogun, Yunifásítì ìlú Èkó àti National Institute for Pharmaceutical Research and Development, tí ó wà ní Abuja, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2006 títí di ṣojúnírínwó ni ó ti jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní éékà tí ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òògùn àti iṣẹ́ òògùn, olùkọ́ ìmọ̀ òògùn, Yunifásitì ìlú Èkó, ní Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2009 sí ọdún 2010, òun ni alága fún ẹgbẹ́ Amẹ́ríkà ti àwọn onímọ̀-iṣẹ́ oògùn (aaps) ìgbìmọ̀ ìgúnnà ẹgbẹ́ (M)..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2009 títí di àkọ́kọ́ yí ni ó ti jẹ́ olùbẹ̀wò olùkọ́ ti Fulbright (Agbaye/ Ilera), ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, Ile Ife ati Ọ̀jọ̀gbọ́n olùbẹ̀wò fún Yunifásítì Nnamdi Azikiwe, Awka, Ipinle Anambra, orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Lákòókò tí ó wà lẹ́nu iṣẹ́ ẹ rẹ̀, Adeyeye ti kọ́ àwọn akẹ́kọ ò gboyè ti Ph.D tí ó lé ní márùndínlógún àti àwọn akẹ́kọ ó gboyè MSC..
wikipedia
yo
Adeyeye ni awon iwe-ẹri marun un, awon iwe afọwọkọ laarin ti awon elegbe se atunyẹwo won, awon ori iwe ati awon iwe, ati awon igbejade ijinle sayensi ti o le ni ogoje..
wikipedia
yo
Ni ojo kokanla osu kokanla, odun 2017 ni won daruko Adeyeye gege bi i oludari gbogbogbo fun ile ise ti o n ri si isakoso oogun ati ounje (National Agency for Food and Drug Administration and Control) lati rọpo Ademola Andrew MAineri.Awon ami eye ati Ola Mojisola Adeyeye ti gba awon ami eye lóríṣiríṣi..
wikipedia
yo
William Fulbright Scholar for African Regional Research Program lórí àrùn AIDS àti àwọn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ tí ó farajọ àrùn AIDS.Ní ọdún 1991/1992, Wọ́n kọ orúkọ rẹ̀ sínú ìwé Marquis Who's Who of American Women.ní Ọdún 1983, Graduate Fellowship by the American Association of University Women (Aìtànná). Ìwé-àṣẹ Christianah M Adeyeye, Vicki l Davis, Udáyà Ktreka..
wikipedia
yo
In situ gel Ophthal2 Drug Derovery system of estradi or other estrogen for Prevention of cataracts..
wikipedia
yo
United States PANene US 2011 US PANeLọ́dún 8,fìfẹ́, Christianah Moji Adeyeye, Anjali joshi and Fred Esseku..
wikipedia
yo
Anti-retroviral Drug formulations for Treat of Children exposed to HIV/AIDS..
wikipedia
yo
Pct/us2009/031285 Christianah Moji Adeyeye and Ashwin Jain, controlled release pharmaceutical preparation for Treat of EnabúléàṣeyọríKristẹni and FIcystic Brea disease., U.S..
wikipedia
yo
May 6, 2003 Christianah Moji Adeyeye, hideki ichi and yoshinstiòbu fukuMori, method of Tngdọgba a patient with a pro!’ time-release drug and the drug itself, U.S..
wikipedia
yo
6,156,340, December 5, 2000.Ìgbésí ayé rẹ̀ Adeyeye ṣe igbeyawo pelu Senator Olusola Adeyeye ti Agbegbe Osun..
wikipedia
yo
Wọ́n bí ọmọ meji, ọkunrin kan ati obinrin kan.Inurere ati iṣẹ agbegbe Adeyeye ni oludasile ẹgbẹ ti ko wa fun ere jije ti won si n se iranlọwọ lori awon oogun fun arun AIDS ati awon alaisan ti o ni arun AIDS ni orile-ede Naijiria.Oun tun ni oludasile Sarah awọn idile ti o gbooro sii fun awon ọmọde, eyi ni ile ti o nse itoju awon omo wẹẹrẹ lati ile-iwe jẹ́léosimi titi de ipele ile-eko giga Yunifasiti..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ yí i fìdíkalẹ̀ sí ìlú Òṣogbo, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun àti Ògbómọ̀sọ́, ní Ìpínlẹ̀ Oyo.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn aláàyè..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ ẹ̀yẹ Best Supporting Actress láti ọ̀dọ Africa Movie Academy Award.Ìgbésí ayé rẹ̀ àwọn òbí njàmah jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Cameroon..
wikipedia
yo
Ó gboyè jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Olabisi Onabanjo University nínú ìmọ̀ èdè GẸ̀Ẹ́SÌ..
wikipedia
yo
O da ẹgbẹ House of Empress kalẹ̀ láti ma ṣe itọju fun awọn ọmọde.aṣayan awọn ere ti o ti ṣeawọn itọkasi..
wikipedia
yo
Femi Taylor (Bii ni ojo kejo osu kerin odun 1961) je onijo ati osere ni orile ede Naijiria ti o gbajumo fun ipa epo ti o ko ninu ere return of the Jedi ni odun 1983..
wikipedia
yo
O ko ipa tantomi ninu ere orin ti cats ni odun 1981..
wikipedia
yo
Femi jẹ iyawo fun Clauis Skytte Kamper, o si ti bi ọmọ meji.Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣeàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
O gba ami eye Revelation of the Year lati odo Nollywood Awards ní ọdún 2012.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Lawal sí ìlú Badagry..
wikipedia
yo
Ó gboyè nínú ìmọ̀ Creative Arts láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Yunifásitì ìlú Èkó.Iṣẹ́ ò kópa nínú ìdíje next movie star àmọ́ kò yege níbẹ̀..
wikipedia
yo
O bẹrẹ ere sise ninu ere Sllow Waters, o si ko ipa Chioma ninu ere naa..
wikipedia
yo
Lawal di gbajúmọ̀ nígbà tí ó kó ipa Chinny nínu eré Tinsel..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, ó gba àmì ẹ̀yẹ Revelation of the Year láti ọ̀dọ bọ̀n Awards.Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣe Holding Hope a Time to heal a Tofọ́n to heartbreak Emem and Angie Madam's pa àkọsílẹ̀d Web Millenium Parent Desperate Baby Mamaawọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Bose Ogulu je onimo, Solaawon ati alámòójútó omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun ni o boju to iṣẹ orin fun gbaju-gbaja olorin Takadufe Burna Boy ti o tun je omo re..
wikipedia
yo
Oun ni gbogbo eniyan mo si Mama Burna.ibẹrẹ Aye re Ogulu je okan lara awon omo LÁMÈYÍ olorin ile [[Naijiri] tele, iyen Benson Idonije, ti oun naa tun je alámòójútó ise orin fun ilu-mooka olorin omo orile-ede Naijiria Fela Kuti..
wikipedia
yo
Ogulu eko gboye b.A ninu imo ede agbaye (foreign languages) ati iwe eri keji (Masters of Arts) ninu imo isogbu ni ile-eko Yunifasiti Port Harcourt..
wikipedia
yo
O ti sise gege bi ogbufo fun ile-ise okowo ti apa iwo oorun ile Afirika..
wikipedia
yo
Ó gbọ́nèdè Gẹ̀ẹ́sì, Faransé, Jámánì Italy àti èdè Yorùbá dunjú-dunjú..
wikipedia
yo
Ó dá ilé-ẹ̀kọ́ kan tí ó pè ní she then rán a language school called language Bridges, where she organized cultural immersion trips for over 1,800 young people..
wikipedia
yo
O je oluko ede Faranse fun odun die ni Yunifasiti Port Harcourt, ti o si feyin ti ni odun 2018.ise re Ogulu ni o n samojuto ise Oijoba omo re damini ti oruko inagijẹ re Burna Boy ati omo re obinrin ti o n lo oruko re Nissi..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó gbọ́ wípé ọmọ rẹ̀ Burna Boy ti gba àmì-ẹ̀yẹ tí MTV fún ọ̀kọrin tó peregedé jùlọ ní ọdún 2019, inú rẹ̀ dùn, ó sì fi tayọ tayọ dá ayẹyẹ náà dúró láti sọ̀rọ̀ .Nígbà tí Burna Boy gba àmì-ẹ̀yẹ mẹ́rin ní ibi ayẹyẹ Soundcity MVP Awards Festival ní ọdún 2018, Ogulu lo lo gba ami-eye naa lorukọ ọmọ rẹ̀, èyí sì FA ọ̀pọ̀lọpọ̀ Dama-wúyẹ́ ní orí àwọn ikani ibaniDoré gbogbo paa paa jùlọ akori "expect more ìdánáce" tí wọ́n FI sí orí ẹrú ayélujára LÓRÍ Ọ̀RỌ̀ NÁÀ
wikipedia
yo
Bose Ogulu ni alase ati oludasile ile-ise Spaceship Collective , ti o je ile-ise Igborin..
wikipedia
yo
àti ilé-iṣẹ́ ìtẹ̀wé ti Spaceship Publishing.Ìgbé ayé rẹ̀ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ọ̀gbẹ́ni Samuel Ogulu fun ogbon odun, Olorun si fi awon omo meta damini, Foja, àti Nissi Ogulu jíǹkí won.Àwọn itọkasi Nigerian women in ìdánásáwọn ènìyàn alààyèMusic ManarsNigerian Women Educators of birth missing (living People)..
wikipedia
yo
OLUWAKemi Nina Sosanya (bíi ni ojo kefa osu kefa odun 1969) je osere ti o gbajumọ fun ipa ti o ko ninu ere w1a ati Last Tango in Halifax.ibẹrẹ pepe aye ati eko rẹ won bi Sosanya si ilu Islington ni London..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Britain..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Vale of Catmose College ní oakham.Ise Sosanya ti kópa nínu oríṣìíríṣìí eré orí ìtàgé, fíìmù àti eré Ori Oriwesókè..
wikipedia
yo
Ere Ori Itage ti O koko fi di gbajumọ ni ere Anthony and Cleopatra ati ere Teachers ti wọn ṣe ni ọdun 2001..
wikipedia
yo
O ti kopa ninu awọn ere bii Sorted, People Like Us, Make Me Famous, Love actually, Nathan barley, The VOte, Renaissance, Casanthe, Three Gamblers, Much Ado About Nothing, Cape Acdth/Meadow, the Doctor Who Episode Fear Her, ati FM.Ni ọdun 2003, o ko ipa Rosalind ninu ere as You Like It..
wikipedia
yo
Ní ọdún, ó kó ipa Rosaline ninu eré Love's Labour's lost..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, ó ṣàfihàn nínú eré Young Chekópa, ó sì kó ipa Laura Porter nínu eré Marcella.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Rukáyà Akínsànyà (bíi ní ketalelogun Oṣù Kẹjọ Ọdún 1984) tí orúkọ inagi rẹ̀ jẹ́ Ṣélix Sanda jẹ́ òṣèré àti adarí eré ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 2004 nígbà tí ó sì wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Lagos State University..
wikipedia
yo
Òun àti òṣèré Boláńlé Nọba jẹ́ mọ̀lẹ́bi.Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣe Lethal Woman (2008) obscure Molsves (2009) Loonyo (2012) Miami Teve (2012) Lèting My Man (2013) White Chapel The Seekers Legal War Campus Love Leve My Man (2013) Gold Dice Oce What's Within the relationship (2016)Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Folake Olowofowokuku (Bii ni ojo kerindinlogbon osu kewaa odun 1983) je osere ati olorin ni orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ó kópa nínu eré Bob Hew AbiShola ní ọdún 2019.Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹpẹ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Olówófọwọ́ku sí ìdílé babaTunji Olowofọwọkuku àti Felicia Olowofọwọkuku
wikipedia
yo
Ó gboyè nínú ìmọ̀ eré orí ìtàgé láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti City College of New York.Iṣẹ́ lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní Off-Broadway Theatre ní ìlú New York..
wikipedia
yo
Olówófọwọ́ kó ipa àsárór MVA Jefferson nínu eré Death race 2050 ní ọdún 2017..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kesàn-án ọdún 2019, ó kópa AbiShola nínu eré Bob Hew AbiShola.Ó gboye ninu imo Audio Engineering lati Odò Institute of Audio Research..
wikipedia
yo
Ó kópa nínu eré orin The Stars (are Out Toñight) àti The Next Day ní ọdún 2013.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
O gbajumọ gẹgẹ bi araparẹgangan fun ipa ti o ko ninu ere Sapo ni ọdun 1999 eyi ti Tunde Kelani gbe jade.ibẹrẹ pepe aye ati ẹkọ rẹ wọn bi kafidi ni ojo kokandinlogbon osu keje..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Abeokuta Grammar School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Olabisi Onabanjo University nibi ti ó ti gboyè nínu imọ̀ Mass communication.Iṣẹ́ Jukábì bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe pẹ̀lú eré The White Handker..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ nígbà tí ó kópa nínu eré Side ní ọdún 1999 pẹ̀lú àwọn òṣèré gbajúmọ̀ bíi Kunle Afolayan, Peter Fatomilola, Kola Oyewo, Yemi Shodimu..
wikipedia
yo
Ipa tí ó kó nínú eré Àwalẹ́wà ni ó jẹ́ kí ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré gégé tó dára jù lọ láti ọ̀dọ Africa Movie Academy Award..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ó kópa nínu eré dírámà Dazzling Mirage..
wikipedia
yo
O gbe ere ti re jade ni ọdun 2015, o si pe akori rẹ ni Bintu.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Katung adùwàk tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹ́ta ọdún 1980 jẹ́ ẹni tí ó jáwé olúborí nínú ìdíje Big Brother Nigeria ní ọdún 2006..
wikipedia
yo
Wọ́n bí ní ìlú Kańnrì, ní Ìpínlẹ̀ Kàdúná, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ó jẹ́ ònkọ̀tàn, olùgbéré-jáde àti olùdarí eré orí-ìtàgé..
wikipedia
yo
As well as a graduate of political science.O jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìgbìmọ̀ kan ní ilé-ẹ̀kọ́ okòwò "Harvard Africa Business School Forum", tí ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí alámòójútó àgbà ní ilé-iṣẹ́ MTV Base, ó tún jẹ́ adarí àgbà ní ilé-iṣẹ́ "Olùvia", ó sì tún jẹ́ adarí àgbà ní ilé-iṣẹ́ igborinjáde ti chocolate City..
wikipedia
yo
Oun ni alase ati oludari ile-ise one o eight media and African partner for Campfire media.Iṣẹ reBig Brother niaaduwàk gba ami-eye ti Michelle dédé ati Olisa Adibua gbe kale nigba ti o wa ni omo odun merindinlogbon ni odun 2006 pẹlu iye owo ti o to $100,000..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọdún mọ́kànlá, ó fi lédè wípé láti gbégbá orókè nínú ìdíje bayi, àwọn olùkópa nílò ọgbọ́n àti ọpọlọ gidi.Lẹ́yìn ìdíje Big Brother Nigerialeyin idije, aduwak gbéra lọ sí orílẹ̀-èdè New York lati tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ digital Film Academy, tí ó dara pọ̀ mọ́ ṣíṣe sinimá lẹ́yìn ẹ̀kọ́ rẹ̀.Gbígbé eré jáde rèeré tí kò bá jẹ eré tí ó yẹ kí ó gbé àdùwak jáde ní Heaven's Hell..
wikipedia
yo
Ọjọ́ tí wọ́n kéde wípé àwọn yóò gbé eré náà jáde jẹ́ ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kíní ọdún 2015, àmọ́ wọn kò gbé eré náà jáde títí di ọjọ́ kẹwàá oṣù karùn ún ọdún 2019..
wikipedia
yo
Aduwák darí eré kan tí ó ṣàfihàn Ruke rúrú tí ó ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà tí wọ́n tún jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà bákan náà àti àwọn ọmọ ilẹ̀ Prika tí wọ́n ń gbé ní ìlú Okere gbogbo ní ọdún 2020 tí wọ́n pe àrírí rẹ̀ ní Not supposed tó Be Here.Igbe ayé rẹ̀wáwá ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ní Raven Taylor-wá, wọ́n sì bí bí ọmọ okùnrin kan ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Kẹrin ọdún 2018.Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ Rá Guest (2011) Punv (2012! (2012) When Love (2014) Heaven's Hell (2019) Not supposed tó be héh (2020) rẹ̀ "Superstar" – By Ice Prince (2011) Ika Aláwọ̀ka Cine’’ Film Director Stubs Film producer Stubs Nigerian Film Directors Nigerian Film Sace People From from State Nigerian screenting Ọjọ́ìbí ní 1980àwọn ní 1980..
wikipedia
yo
Kemi Adesoye jẹ́ ònkọ̀tàn tí ó kó gbajú-gbajà eré The Figurine..
wikipedia
yo
O si tun ti ko ọpọlọpọ ere onípele lori ero amóhùn-máwòrán bi Tinsel.ibẹrẹ Aye ati Eko Kiku bi Adesoye ni Ipinle Kwara, ni won to ni Ipinle Kaduna..
wikipedia
yo
She is the last of four children.Adésoye fẹ́ràn láti máa wo àwọn eré bíi eré bẹ́ẹ̀berin, eré Adéday, eré oníṣe àti àwọn eré onípele àtìgbà dégbà lóríṣiríṣi..
wikipedia
yo
GẸ́GẸ́ BÍ akẹ́kọ nínú ìmọ̀ Architecture ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó wà ní ọmọ akẹ́kọ, ìfẹ́ tí ó ní sí ìtàn kíkọ ní ó mú kí ó ṣalábàápàdé ìwé kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "The Elements of Script Writing" tí IRWIN R..
wikipedia
yo
lásìkò yĩ, kò tíì mọ̀ wípé wọ́n lè fi ìtàn kíkọ ṣe iṣẹ́ òòjọ́ ẹni..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Federal University of Technology, Minna, ní Ìpínlẹ̀ Niger láti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè Ikeji nínú ìmọ̀.Nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ ìwé kíkọ..
wikipedia
yo
Oríṣiríṣi ìpèníjà ni ó kojú látàrí àìsí ilé-ẹ̀kọ́ tí ó ń kọ́ni nípa ìtàn kíkọ́ nígbà náà.Lẹ́yìn tí ó ṣàkíyèsí ìfẹ́ rẹ̀ sí ìtàn kíkọ ni ó bá bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ́ nípa bí a ṣe ń kọ ìtàn àpilẹ̀kọ ní orí ẹ̀rọ ayélujára, tí ó sì tún lọ kọ́ nípa bí a ṣe ń kọ nípa ìtàn àpilẹ̀kọ ní New York Film Academy ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.Iṣẹ́ rẹ̀lẹ́yìn tí Adésoye jáde nílé ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ rédíò fún bí ọdún márùn ún..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ibi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ tí Ifba International Film and Broadcast Academy, níbi tí ó ti kọ́kọ́ mọ̀ nípa iṣẹ́ àkànṣe tí wọ́n pè ní "New directions" tí MNET ṣagbátẹrù rẹ̀..
wikipedia
yo
Lásìkò yí, ilé-iṣẹ́ yí n wá ẹni tí ó lè kọ ìtàn ṣókí fún wọn, ó sì kọ ìtàn kékeré kan fún wọn tí ó pè ní "The Special Gèlè" *
wikipedia
yo
Wọ́n mú Ìwé Ìtàn Rẹ̀, Lóòtọ́ kò gbébá orókè nínú ìdíje yí, àmọ́ ó ní ìfọkànblálẹ̀ wípé ọjọ́ ọ̀la rẹ dára..
wikipedia
yo
Ó kópa nínú ìdíje yí ní ọdún méjì lẹ́yìn , ó sì jáwé olúborí nínú ìdíje náà ler\ léra..
wikipedia
yo
Eré yí ni ó fún òòò ní ànfàní láti bá àwọn Nàìjíríà Nàìjíríà nídi iṣẹ́ sinimá bi Amaka Igwe pàdé..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó di ònkọ̀tàn fún ilé-iṣẹ́ DSTV, tí ó sì n kọ́ àwọn ìtàn eré bi Doctors Quarters..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọ̀ rẹyìn, ó ṣaláìbapàdé gbajú gbajà olùgbéréjáde Kúnlé Afọláyan, ó kọ́ eré abanilẹ́rù the Figurine fún ti eré náà sì gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ bí Africa Movie Academy Awards lẹ́yìn tí wọ́n gbé jáde tán.Látàrí àṣeyọrí eré The Figurine, Adésoye di ẹni ayé ń fẹ́ pàá pàá jùlọ ní àwùjọ Nollywood gẹ́gẹ́ bí òǹkọ̀wé..
wikipedia
yo
Sokari ekìnẹ je ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Blogger àti òǹkọ̀wé..
wikipedia
yo
O sise oniroyin ni PAmbazuka News ti o sin ti kowe fun Feminist Africa ati New internatimption..
wikipedia
yo
Ekìn ti fìgbà kan ní ìkànnì ìtakùrọsọ ayélujára láàárín ọdún 2004 àti 2014, níbi tí ó ti máa ń tàkúrọ̀sọ nípa ẹ̀tọ́ obìnrin, ètò ìbálòpọ̀ akọ àti akọ, abo àti abo, àti ọ̀rọ̀ nípa àwùjọ..
wikipedia
yo
Ó ti dìjọ kọ̀wé pẹ̀lú àwọn òǹkọ̀wé mìíràn, bẹ́ẹ̀ ló ti ṣe lámèyítọ́ fún ìwé mẹ́rin, ó sìn tí ṣe olùkọ́ àwọn ọmọdé ní Haiti..
wikipedia
yo
O dagba si Nigeria, ṣugbọn nigba to ya, o kọja si England lati lọ kẹkọọ sii..
wikipedia
yo
ó kàwé gboyè dìgírì nínú ìmọ̀ sáyẹ́nsí ìmọ̀-èrò tuntun àti dìgírì nínú ìmọ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ ní University of London.Ẹẹ̀kìnẹ gbé ní Amẹ́ríkà fún àìmọye ọdún kí ó tó padà sí United Kingdom, níbi tí ó ti gba iṣẹ́ olùkọ́ Yunifásítì ..
wikipedia
yo
Fati lámì Abubakar tí wọ́n bí lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1951 (12 April 1951) jẹ́ adájọ́ àgbà ìpín Niger, obìnrin àkọ́kọ́ fún Nàìjíríà àti aya Ààrẹ-àná, Abdullámì Abubakar lọ́dún 1998 sí 1999..
wikipedia
yo
Ó di adájọ́ àgbà ní ìpín Niger lọ́dún 2013 sí 2016.Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí Fati lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1951 ní ìlú Minna, ní [[Ìpínlẹ̀ Niger] [lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ó kàwé ní Queen Elizabeth School ní [[Ìlọrin], ní ìpínlẹ̀ Kwara..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà, ó kàwé ní Federal Government College, ní ìpínlẹ̀ ṣòkòtò, àti ní Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University, ilé Ifẹ̀, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́..
wikipedia
yo
Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin, bẹ́ẹ̀ náà ló kàwé gboyè ọ̀mọ̀wé nínú ìmọ̀ philosophy..
wikipedia
yo
Bákan náà, Fati kàwé gboyè ní ‘Nigeria Law school'.Ìgbésí ayé rẹ̀ lọ́tọ̀Fati lámì fẹ́ Ààrẹ àná, Abdullámì Abubakar, wọ́n sìn bí ọmọ mẹ́fà fún ara wọn.Àyè rẹ̀ Abubakar ti fẹ́ Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí, Abdullámì Abubakar, ẹni tí ó bí ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Fati Abubakar jẹ́ gbajúmọ̀ oníròyìn aláwòrán àti àfohun-fàwòrán nínú ètò..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọbìnrin ọmọ bíbí Maiduguri, ní ìpínlẹ̀ Borno orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní bi tí ó gbajúmọ̀ dé, ìwé-ìròyìn The New York Times, CNN Africa, BBC àti Voice of America ṣe atejade iṣẹ́ rẹ̀.Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ Fati jẹ́ ògidì ọmọ bíbí ìlú Maiduguri, ní ìpínlẹ̀ Borno lórílẹ̀-èdè Nigeria.Gbajúmọ̀ àti ògidì nínú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ní àwọn pàgbankọgbì àwọn ìwé ìròyìn òkè-òkun The New York Times, CNN Africa, BBC àti Voice of America ti fìgbà kan tẹ̀ jáde nínú ìwé ìròyìn wọn..
wikipedia
yo
O sise lati se agbekale lori làálàá ati isoro ti o doju ko ipinle Borno, paapaa ju lo, wahala awon agbesùnmọ̀mí Boko Haram..
wikipedia
yo